text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Bí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ kò bá tẹ́ wọn lọ́rùn, wọn ma yanjú ẹni náà ní ojúbọ ni. Àwọn ohun wọ̀nyìí tí wọ́n ń ṣe, ni láti dẹ́kun kí wọ́n yé kó àwọn èèyàn wọn tí wọ́n lọ ń tà sí oko ẹrú.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ase Edunmare, ojumo to mo loni ire ni ko ja si fun wa http://t.co/gH9NKP5NVo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jagajìgì ò mọ ogun; ogun ńpa elégbèje àdó.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹnu ìloro, ìyẹn àbáwọlé/ẹnu-ọ̀nà ni a ó fi ọwọ̀ (ìgbálẹ̀) méjìi nì kọ́ sí, bí ọlọ́ṣà bá wọlé pẹ́rẹ́n, ó kẹ́ran nù un! #OwoFunOle #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user # Omo Yoruba atata! Oodua a gbe e o!"""" Àṣẹ o!!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user e pele! A o ni ri iru adanwo bayi mo! Esa gba fun Eledumare! Ki lo wa kan bayi?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí n má bọ̀ọ́ sọ́wọ́ ìkà, kí àwọn aṣebi máà rí mi gbé ṣe, kí n máa lọ 're, kí n máa bọ̀ọ re.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ire owo ire ọmọ èwo ló tún kù ẹyin èèyàn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
egbe ori yin soke eyin ilekun ayeraye ki a gbe yin soke ki oba to po ni ipa ati agbara ogo anuibukun ati oreofe wole wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
láì mọye ìgbà ni mo ti so bí nǹkan ti ṣe wà àti ìyẹn àwọn ti bí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user Íjọba ìpínlẹ̀ Kaduna ti kéde kónílé ó gbélé lórí ìjà https://t.co/DiKQE4iyrS
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user mo wa fi owo dodo pa omo oni dodo ni Idoodo. #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ilorin Afonja. Enu dun ju'yo https://t.co/YMx40MwZB7
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nítorí wípé ọ̀pọ̀ òjò ló ti rọ̀, tílẹ̀ ti fà mu. Ọ̀pọ̀ omi ló sì ti gba abẹ́ afárá kọjá. Àwọn kan lọ wọn ò padà wọlé. Òṣùbà rẹ Ọlọ́run.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ere tó dára púpọ̀ fún àwọn ọmọdé láti wò. . . . . Ere tó dára púpọ̀ fún àwọn ọmọdé láti wò ni Mirror Boy. Ere tó dùn tí a ṣe dáadáa tó sì kọ àwọn ọmọdé lẹ́kọ̀ọ́ ni ere yìí. Orin inú ere náà rẹwà ó sì dùn láti gbọ́.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Idije Gomina Ni Ipinle Osun @user Bibi Ire Ko Se Fowo Ra! http://t.co/tTeqf4v9BD via @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user èyí wà lẹní ò sí nǹkan! Irú èyí là ń fẹ́ ní #Nigeria wa yìí, tiwantiwa, fún ìdàgbàsókè ìlú wa. #Yoruba #ORIKI #Ipara
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
... òní àwọn ìran mọ́nıgbàgbé, ṣùgbọ́n ó kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ kùdìẹ̀ kùdìẹ̀ tí kò fi ìdarí tó bá òde òní mú hàn.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ̀rọ̀ o Ọba mí, òjò lá fẹ́ o a fẹ́ ìjì. Ẹ káàárọ̀ o #ekaaaro #yoruba #morning #Lagos #Nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò sí ọṣẹ ìwẹ̀ náà láyé ń bí, ọ̀rọ̀ ẹnu kọ́, 'torí pé ara nǹkan ìṣẹ̀dá ni ọṣẹ dúdú ti wá. #Kemika
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A: Bí a bá wá rí èyí tó ní ṣọ́ọ̀ṣì tàbí mọ́ṣálááṣí lòun fẹ́ẹ́ máa lọ nínúu wọn ń kọ́? ỌOA: Wọn wà, kódà, mo ti fi wọ́n gégùn-ún pé ẹni tó bá lọọ ṣe nǹkan mìíìn yàtọ̀ sí èyí tí mo ń ṣe yìí, tó bá lọọ darapọ̀ mọ́ ẹ̀sìn kan, tó lọọ...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo lè fí ọwọ́ mi sọ̀yà pé sinimá àgbéléwò dùn ósì dára láti wò. Mo gbóríyìn fún sinima agbelewo yìí púpọ̀ eré aláwádà ní fún àwọn ọmọwé. Eré tó panilẹrin tó mú ọkàn ẹni tó nwò kún fún ayọ̀.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Odo ni awon mejeeji. Jeki won gbadun ara won #TweetInYoruba! https://t.co/3LbEqe907p
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Àwọn tí wọ́n torí ìnira ọrọ̀-ajé má bímọ, njẹ́ a lè dáwọn lẹ́bi? Àbí ọmọ bíbí pọn dandan gẹ́gẹ́ bí àṣà wa?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user ,to bà ya ni sin yi....wan atun ni awon o sò bè ô!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwò tó dìpò ódàbí oun tíkò wọ́n tó ní nkan tó pọ̀ tó jẹ́ asán láyìká oun tó kéré
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ilé tí a f'itọ́ mọ; ìrì ni yóò wó o. *Báwo ni ilé tí a fi itọ́ ẹnu mọ ṣe fẹ́ dúró sánsán? Bí ìrí bá ṣẹ̀, ó di gbàgà! #EsinOro🐎 #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú àmọ́júbà Ẹ̀ta Ọdún (Bélú) o! A ti rí èyí náà, a ó rí ẹ̀mìíìn tẹbí tará! #OdunNLoSopin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Ewì____ ni """"""""Ọmọ mi ò, akúrúbete kúrú bete, ọmọ ò, a kùrùbété kùrùbété, bíò kú o máa raṣọ fún ẹ... A. Amúṣẹ́yá B. Arẹmọ́lẹ́kún #ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó n ṣe ní àánú, fíìmù náà nígbàgbogbo jẹ́ dáradàra àti onílọ́ra pẹ̀lú díẹ̀ nínú àwọn àkókò ọ̀ṣẹ̀ ọ̀sán púpọ̀ ti ìfihàn ẹ̀dùn.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ẹ ẹ̀ bámi dúpẹ́ lọ́wọ́ Ilé-iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì Abẹ́òkút. Àwọn ni wọ́n ṣe irú ànfàní yìí. http://t.co/sZB4VSn2
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré naa dára ṣùgbọ́n ófi wákàtí méjì ṣ'òfò
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àwọn gómìnà ń ṣe ìgbéyàwó fọ́mọ wọn nígbà tí Boko Haram ń ko àwa lọmọ lọ"""" Olóòtú Sahara Reporters tí fọgba yángan https://t.co/PKnjtThIZ6 https://t.co/Nl5Ssd9tws @user @user #Yoruba #OlayemiOniroyin
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Akuu odun Ajinde .. #kaftantv #kaftantvyoruba #kaftan #yoruba #yorubaculture #yorubanimi #yorubalanguage #instagram #africa #african #nigeria #lagos #ekiti #ondo #ogun #oyo #ibadan https://t.co/TuzAYYI13q https://t.co/q3Scl0K3py
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré Itokasi. . Fíìmù to pe. Mo feran gbogbo iseju aaya Fíìmù na, Mi ko fe ko pari mo.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
gan àìrọrùn.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
lati ṣalaye lẹẹkansii jọwọ tumọ itumọ yii fun ẹri gbigbe lọ ti awọn ami iṣẹ lati ni iye wọn gbọdọ ni iye o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
afi ki olohun gba wa lowo won ẹ̀yin ìjọba ẹ yẹ ira yín wò o |
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó ṣòro fún ọmọadúláwọ̀ láti ṣe ìrìnàjò jáde kúrò ní ilẹ̀adúláwọ̀ ṣùgbọ́n bẹ́ẹ̀ náà ni ó nira láti rìnrìnàjò láàárín ilẹ̀ náà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
N kò ní fẹ́ sọ wípé wọ́n ṣe àwọ́n àṣìṣe ni. Bí ìgbà tí àwọn aròbó ilé ẹ̀kọ́ ọmọwẹ́wẹ́ bá kan tó eré papọ̀ ni.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Awada Nollywood gbòòrò nìkan ni ipò ṣe o ni ì́dánilójú nítòótọ́.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Mo sín in yín jẹ ni. Ẹ̀yin eléèbó ì í kú 'lé.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÀWỌN AYẸYẸ ÌBÍLẸ̀ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ ÀTI ÌGBÀ TÍ WỌ́N Ń ṢE WỌ́N (2): Ọdún Ṣàǹgó (Gbogbo ilẹ̀ Yorùbá) - Oṣù Ògún Ọdún ÒGÚN Àjọbọ (gbogbo ilẹ̀ Yorùbá) - Oṣù Ògún Ọdún IFÁ; ìbẹ̀rẹ̀ ọdún titun fún àwọn Yorùbá; (gbogbo ilẹ̀ Yorùbá) - Oṣù Òkúdù
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àgùtàn tó fẹ́ máa dún bi ìkokò á múra sílẹ̀ fún ọfà ọlọ́dẹ a sheep that wants to howl like wolves should be expect
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ọkọ̀ á rèfò, ẹ kí wọ́n nílé Olúyọ̀lé.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Watch #jkf @user as he #speaks #Yoruba on #Ekiti perspective on #grazingland """"""""Ipese Ile fun Eran dida"""""""" https://t.c…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀pàpà paradà ó dèèmọ̀ gòdògbò taani ò mọ̀ pẹ́nu àgbà òṣèlú lèèmọ̀ ti ń gbó àgbà òṣèlú, àgbà ọ̀jẹ̀lú https://t.co/3GDAByaS6r #Atelewo #YorubaLiterature #Yoruba #politicians
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nínú ìwé rẹ̀ #InAfricasForestAndJungle #SixYearsAmongTheYoruba R.H Stone tú pẹẹrẹpẹ́ẹ̀rẹ̀ oun ojú rẹ̀ rí. @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Lọ́rọ̀ kan, iṣẹ́ àgbẹ̀ jẹ́ 'kan ń'nú ohun t'ó fà á tí àwọn bàbáa wa fi láya t'ó pọ̀. #AyaPupoLaarinYoruba #Asa #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́jọ́ kan aatren
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àṣemọ́jú ni wọ́n kúkú ṣe ayẹyẹ ọ̀hún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Torípé wọ́n mọ ihun wọ́n ń ṣe, àwa ló pàpà wá bájà, ọgbọ́n àti ta àṣà ti wọ́n fún wa ni gbogbo ẹ. #Superstition
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
odi igba ti won ba gbegba oroke ki emi to yin wonigba naa ni moma mo boya super eagle niwon toto tabi super chicken esther adejoke
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré to yanilenu tí a gbọ́dọ̀ wo.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user òun nìkan kọ́ ni ẹ̀sùn yìí kàn o, ṣàṣà nínúu wọn lọmọ wọn ńbẹ̀ lókè òkun ìsàlẹ̀ ọ̀sà. Ni ọ̀rọ̀ ìlú yìí ò f…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Falano o Gbo Ti E @user ti gba ise lowo @user ati @user Ngozi ni ohun ti ko Ibon awon ologun wolu o http://t.co/uKNXMsovuD
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
za mu ci gaba da fitar da yan ɓoye da ɓarna daga duk inda suke ɓoye domin a yanzu muna da karfi da kuma kyawu fiye da da a yoo tẹsiwaju lati mu siga awọn looters ati awọn arekereke lati ibikibi ti wọn tọju nitoripe a ni okun ati dara julọ ni igbagbogbo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó ṣòro láti jẹ́ ọ̀lẹ̀lẹ̀ gbígbóná inú ewé, ni a fi ń mú ọ̀lẹ̀ jẹ níbi tí ó pẹlẹbẹ, ibi tí ò gbóná jù. https://t.co/HxIFG9PFWZ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ekaaro eyin olujumo mi Ni gain. Se daadaa la ji. E Ku OSU titun Erena yii. OSU na a san wa si ire. #TweetYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
2. Bí a bá ní pé: 'a pa iṣu ní odó', kí ni a fẹ́ sọ ní pàtó? #Ibeere #Yoruba #AkanloEde
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo kí kú àyájọ́ ọdún kẹrìnlá o àṣèyí ṣàmọ́dún o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àsejù àti àìní òtítọ́ ni ó pa eré náà kú.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Irọ́ baba irọ́! Olé, baba olé! Èké baba èké! #Britain #Europe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Superstition náà lọ́ pe ohun gbogbo, kí a ba lè gbàgbé ohun ìníi wa. #Superstition
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn kò le dára jù báyìí lọ!. . . . Ó dàbíi tòọ́tọ́ púpọ̀. Ó fi ìtàn àti ìgbésí ayé àwọn òdókùnrin Nàìjíríà tí ó ń gbé ní Èkó.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n awòràwọ̀ ní ó tún di bíi ọdún márùndínláàádọ́fà kí ìṣẹ̀lẹ̀ yí tó tún wáíyé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bọ́tọ ni à ń lò fi rẹ́ ilé alábàrá láyé ijọ́un tí kòkòrò kan ò ní wọlé. #Eleboto
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré yii jẹ́ eré tí ètò rẹ̀ dára jù lọ lára eré Nollywood. Ṣe ló jọ eré Afíríkà àti Amẹ́ríkà. Eré ṣíṣe inu rẹ̀ nẹgba, ótún wá yani lẹ́ nu torí pé eré àkọ́kọ́ tí òsèré asíwájú kọ́kọ́ kó pa ninu rẹ̀ ni. Mo júbà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Eniìtàn Adéyẹyẹ̀ Ògúnwúsì láti ìdílé Gíẹ̀si, ọmọ-ọmọ-ọmọ Ọba Dérìn Ọlọ́gbẹ́ńlá 1880-1894 ni #Ooni #Ife kàn. #Yoruba https://t.co/6GmyDjlVmf
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user o se o jare amo o to ijo meta sa, se daadaa ni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
iya omo kilo fun omo re oun fi iku sere igi ibepe ti o le se lo ngun. Kwam1 - Omo Instrumental. I tried. Someone correct me 🤦🏾‍♂️ #Nigeria #yoruba #fuji
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo kíi yín o ẹ̀yin olólùfẹ́ẹ mi tọkàntọkàn ara ò le bí a sì kú iṣẹ́ òní ní báyìí ẹ jẹ́ ká la ara wa lọ́yẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojúmọ́ t'ó mọ́ mi lónìí, ojúmọ́ ire ni kó jẹ́. Ojúmọ́ ayọ̀. Ojúmọ́ ìdùnnú. Ojúmọ́ ọlá. Ojúmọ́ àlàáfíà. Ojúmọ́ ire ni!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ọmọ Yorùbá l'emi ó 👑#TweetInYoruba. https://t.co/5qFYONH7sr
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo fẹ́ kí ẹ wá sí ayẹyẹ mi nínú oṣù kẹ́rin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user beeni sabon gari. Ni kaa kiri ilu yooba lati ri #sabo agbegbe ti awon #hausa tedo si abi ti won po si lo ma ng…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ati mu ileri wa se
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eegun ayeraye niyen rt ti eyan ba fi tipa ba omo molebi tabi ara e lopo ki lo ma se
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user 1.Sún kererere, fà kererere àwon mótò, 2.Ídòtí àti òórùn, 3.Òwón gógó ilé #SuperDriveTimeShow #Tweetin…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#SheikhAlimi ni ọba #Fulani àkọ́kọ́ tó jẹ ní ìlú Ìlọ́rin lẹ́yìn ọba Àfọ̀njá #Ilorin
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
famoodun gbena wojuu diekola o ni ko huwa bii agba tolulope emmanuel
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
⠀ ⠀ yorùbá words of the day⠀⠀ ìjáfara delay noun jáfara to delay verb ⠀⠀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A kú iṣẹ́ẹ tòní o. Ayọ̀ là bá jáde rẹ̀ yó jẹ́ fún wa. Ilẹ̀ ọ̀la tún mọ́ tán, Ọ̀báńjìgì á wà pẹ̀lúu wa. A ó jì í láyọ̀. Ó dàárọ̀!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Irúu ẹ̀wà kékèèké kan ni 'sèsé', ó wà ní funfun àti pupa. A tún ń pè é ní 'àfàtó', a máa korò díẹ̀ lẹ́nu #Idahunsiibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#tweetinyoruba Awon a soju aiye ori Twitter. Oyinbo ni gbogbo won so lori ago. Won a wa si Twitter, won a ma pariwo Yoruba.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Alàgbà ni mí kìí ṣe Ogbeni"""" Yemi Akinwonmi Igbakeji alaga àpapọ̀ fún Gúúsù nínú ẹgbẹ́ òṣèlú @user lo fariga fun @user @user https://t.co/mq432kA3Cw
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sampala ati aadun àgbàdo ️ ẹ̀kọ́ ògì àti
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: @user ó parí. #Achebe #Soyinka"""""""" Bi a ko ba gbagbe oro ana, a ko ni r'eni ba s'ere! E je ka g ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #TweetinYoruba Ikilo pataki fun eyin ti eba fe gbe Iyawo aloku si ile. https://t.co/b2gzF96M2S
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí ọwọ́ ẹni ò bá tíì tẹ èkù idà, a kìí béérè ikú tó pa baba ẹni. Lo dífá fún #Luke #Skywalker http://t.co/V0in9kkKTr
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user A ṣì ń retí orin ìbílẹ̀ tí ẹ kọ pẹ̀lú @user o! Ẹ ti fi ojúu wa sọ́nà tó o! #Yoruba @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìrẹ̀sà wà ní ọ̀kẹ́ ẹgbẹ̀rún sí ìlàoòrùn ọ̀gbómọ̀ṣọ́ orísun ìmọ̀ yìí adegbite folaranmi adewuyi onipede kayode joseph igbon iresa ikoyi a prehistoric relationship till present time in historical research letter vol
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀sìn náà bá kọ́kọ́ bí/pa, ẹni tí ó ni ẹran náà, ló ma kó gbogbo rẹ̀. Èyí tó bá pa/bí leyin ti àkọ́kọ́, àti alágbàsìn, àti olówó ohun ọ̀sìn náà, ní wọ́n ma jọ pín ọmọ wọn dọ́gba. Ọ̀nà àgbàsìn yìí fún àwọn Ọlọ́rọ̀ láti ní oríṣi ohun ọ̀sìn káàkiri ọ̀dọ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Gege bi mo se so, o wulo fun iwadi. O tun wulo fun ifagagbaga eko pelu awon akeko ni ilu mi.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìdí iṣẹ́ ẹni la ti ń mọni lọ́lẹ má jáàfira iṣẹ́ ọmọ aláṣelá yá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
apaadi are broken pieces of a clay pot akufo ikoko alamo ni won npe ni apaadi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọpẹ́ ló yẹ Ọ́ o Ọlọ́run Ọba.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọba ajíni lójú apani, Ọba atúni lọ́wọ́ adeni. Bàbá mi àgbà Arán'ni báni dé'bẹ̀, Ẹ káàárọ̀ o. Mó jíre #Yoruba #goodmorning
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Moh ni Ife reh!! #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀yin ọmọ lẹ́hìn Krístì, ẹ kú ìpalẹ̀mọ́ ọdún. Ṣé ẹ ti ń ra àpò ìrẹsì sílẹ̀? Kérésì ku oṣù kan báyìí. :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train