text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
hahahahaha ó parí toò kí oní ipad yáa gbé ipad ẹ̀ pamọ́
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: “@user: @user Egbon, ori yin wa nibe ju ju ju. Ajanaku koja mo ri n ka n firi. #ourchangeishere” Taa ba rerin ka …
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Beeni, fun eni ti o ba fee kaa""""""""""""""""@user: @user • Yoruba dun nka!""""""""""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
moferan ede abinibi mi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
2. Ẹ̀wà òtílí àti awújẹ jẹ́ méjì ń'nú ẹ̀ya ẹ̀wà ilẹ̀ wa. Orúkọ wo ni Yorùbá ń pe ẹ̀wà inú àwòrán yìí? #Ibeere #Yoruba https://t.co/773KsGKYv1
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àgùntàn kẹ̀ àdúà wo ni wọ́n nfi ìyẹn gbà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Aje wa fi ile mi se ibugbe. https://t.co/zfDaoMJov0
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ìlu gángan ní """"""""b'Ólúbàdàn bá wọ níkà..."""""""" @user #Iseselagba #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a ti gbo o eyin naa e fi oju sona fun wa o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ilu gangan lati iwo oorun guusu #Nigeria jẹ ohun elo orin ti a n lo lati soro. O da lori iṣẹlẹ naa. O nilo awọn ọgbọn pat…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré to ye fún Wiwo. Ó wú mi lórí.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user @user Ọlọ́run Olódùmarè á gba ọpẹ́ wa o. Ìkórè náà, ire làá fi ṣe. A kò ní kó ìkókúkòó mọ́ ọ o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní ìdà kejì ayá gbọdọ̀ kẹ́ ọkọ rẹ̀ gẹ̀gẹ̀ ó gbọdọ̀ bọ̀wọ̀ fún un gẹ́gẹ́ bíi olórí ilé nítorí ìwúrí ló jẹ́ bí ayá bá mọ̀kẹ́ ọkọ ọkọ ò ní kọ̀ láti máa ṣe ojúṣe rẹ̀ kí ni ká ti pé tìyàwò tí a fún lówó ọbẹ̀ tí kò sebẹ̀ sílẹ̀ dọkọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àsìkò ti tó o! #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user hehe. Bí ẹ ṣe sọ ọ́ tẹ́lẹ̀ """"""""""""""""wá oúnjẹ"""""""""""""""" náà dára bẹ́ẹ̀.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí wọ́n bá ní """"""""Sùúrùlérè"""""""", bíi ti aya ààrẹ wa #Patience kọ́!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ah! mo fẹ́ràn ìlú Ìbàdàn. Ibi wọ́n ti ń jẹ ìgbín yó, tí wọ́n tún fi ìkarahun rẹ̀ fọ́'ri mu. haha. Ẹ nlẹ́ o. #Ibadan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
hehe arọ míì ya òmùgọ̀ ná lóòótọ́ ogun tí kìí pa akin tí kìí pa ojo àfi aláìfọ̀rọ̀pọ̀ràn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ káàárọ̀ ẹ̀yin ọmọ ìyá :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Mo kí gbogbo ọmọ Nàìjíríà...... Ẹ se gírí Ìgbà ara làá búra...... Ojúmọ́ ire ni lónìí o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Èdèe yòrùbá kíkọ láìsí àmìn ohùn kò ní ìtumọ̀. Èyí pọn dandan.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Torí Ọlọ́run báwo ni mo ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe ń wo eré yii.. . . . Gbogbo ara mí wà nínú eré yìí. Mo féràn gbogbo ẹ̀fẹ̀ ẹ. Stella ará bìnrin nìyẹn… òṣèré obìnrin tó jágeree.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ṣebí it was paining us together, we are now healed Olúwa ṣeun 🙄
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Itan tooto yii! O le kenka. . . . Ìtàn ńlá ni ìtàn yìí. Ìtan ìrírí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ adúláwò tí ó wá ní òkè òkun láti ìgbà ìwáṣẹ̀. Inú mi dùn pé arákùnrin wa sọ ìtan tirè, tí ó sì kọ ọ, darí, tí ò tún kópa nínú síṣe rẹ̀. Isé eré Damson dára púpọ̀.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
aseni n se ara re owe afoju to diju to ni oun n sun ni e bii wipe igba ti ko sun nko ki lo ri
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kábíèsí Ọ̀rọ̀mpọ̀tọ̀, ọkùnrin ogun. #Oyo #Yoruba """"""""@user: https://t.co/4Tav6TMlqE""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òfófó ní í pa ẹrú; èpè ní í pa olè; ilẹ̀ dídà ní í pa ọ̀rẹ́; alájọbí ní í pa iyèkan t'ó ṣe ibi. #EsinOro #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Apanilẹ́rin, fíìmù ìfẹ . . . . Mo wò pelu ìrònú pe kò lè dá, ṣugbọn o gba gbogbo akiyesi mi,o jẹ fíìmù apanilẹ́rin. Yíò jẹ́ kí o rẹrìn pẹlu awọn òṣeré náà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
iṣẹ́ ìwádìí fínífíní fi hàn kedere wípé àfọwọ́fà ọmọènìyàn ni ó fa ìyípadà ojú ọjọ́ òde òní kì í ṣe àtọwọ́ olódùmarè wá
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lákòótán, ó dùn bi ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù Nollywood, kò ṣòro láti mọ̀; àwọn alátakò àti àwọn tí ò kin ṣe alátakò kò ṣòro dá mọ.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àwọn ọrúkú wo la tún ń pe ìnàkí #Chimpanzee ní #Yorùbá? #QnA #ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Òwe Yorùbá Ojú tó tí rí òkun, kò lè bẹrù ọsa mọ. Yoruba Proverb The eyes that have seen the seas, can no longer be scared…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user #Nigeria ni mo di'bo fun sugbon eya to ba fe pin, e je kaa se dede, ka f'adura sin won. Ka ranti pe 'to Oluwa n'ile ati ekun re #TweetYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èmi ò rò pé ìsinmi ìjọba àpapọ̀ àyájọ́ yóò ṣẹlẹ̀ láì pẹ́ yìí n ò rò bẹ́ẹ̀ nítorí bí ẹ bá wo ìlàpàèrò tó kẹ́yìn ní ọjọ́ iwájú in future ni ààrẹ kọ sílẹ̀ wípé yóò tó wáyé àbí mi ò ríran dáadáa ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òkè lọwọ́ afúnni ńgbé; ìsàlẹ̀ lọwọ́ ẹni tó ńgbà á ńwà. The hand of a giver is always at the top; the hand of the receiver stays underneath. Giving elevates; generosity pays. #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ JH Doherty àti Sedu Williams, Da Rocha dá ilé ìfowópamọ́sí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Lagos Native Bank ní ọdún 1907. Wọ́n sì ní wípé olówó fowó ṣàánú ní Da Rocha. Bí àwọn èèyàn bá bá ìrànlọ́wọ́ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, yóò bèrè wípé,
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yàtọ̀ sómi ìsun kò sómi mímu tó ń mú ọkàn ẹni balẹ̀ bí i omi ti òjò ni mo ṣe fẹ́ràn gbígbemi òjò tí ò bọ́ sórí òrùlé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Arúgbó tó f'ara sin ìjọba ò rí ẹ̀tọ́ gba tẹ́rùn, àwọn tó wà lẹ́nu iṣẹ́ gan-an alára ò rí owó oṣù Òmìnira 2017 gba. #OmiInira57
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo wo takò Ifẹ̀ mi
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
omodè òni agba ni bo dola nitori obiri laye yiyi lo n yi kani. asiko ni pelu ko si eni ti aye ko ni yi de odo re
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìfẹ́ ara wọn nìkan ni èèbó ní, kí Ọ̀gá ba ṣe b'ó ṣe hùn-ún níbi ọrọ̀ Ajé nílẹ̀ẹ wa ni ó fi lé owó-ẹyọ wọlé. #OwoEyo #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ♫ ..Fadeyi nà wọ́n o, bẹ́ẹ délé ẹ foògùn narí o.. ♫ haha
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Awon olote! Omo Aare Nijeria atijo Dokita Jonatanu oku o! Ebele wa ni America to ohun fi owo Nijeria se yotomi. Ema fi enu pa omo fun olomo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
atótó aréré a ṣì nílò àwọn akópa fún ìdíje ìtàn kúkúrú èdè ilẹ̀ adúláwọ̀ ìwọ náà ṣe ìrànwọ́ fún ìdàgbàsókè èdè yorùbá kí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Iṣẹ́ Olódùmarè àwámârídìí. Àbí ẹ ò rí nǹkan! Ọba tó dá Rájí elépo náà ló dá Rájí aláta. Ó dá àwọn kan kúkúrú bente, ẹlòmíì a sì ga gògòrò bí òpó. Olódùmarè mo ṣí fìlà o! #Yoruba https://t.co/O7EeRGqSiB
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lẹ́yìn ìyẹ̀rẹ̀ Ifá nnì, a ó da ìyèrọsùn àti ẹbu ewé gbogbo tí a jó pọ̀, a ó dáa sínú ìpara, lọ́fíndà tàbí ká pò ó mọ́ ọṣẹ máa fi wẹ̀. #Ife
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Inú ìṣẹ̀ṣẹ ni ẹ̀sìn ìgbàlódé-lonígbà-ńlò ti yá àṣà àti ìṣe, wo ìlànà ẹ̀sìn Christian àti Islam, ó pọ̀ ṣúà. #Iseseday #Iseselagba #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ̀rẹ̀fẹ̀ lásán ni. Ìdí pọ̀ nílẹ̀ Yoòbá, àwọn ìdí wọ̀nyí ni mo fẹ́ jẹ́ káwọn èèyàn dárúkọ. #Gelede https://t.co/5tpCzSq5a4
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ọmọ olóòkú bá ṣe pọ̀ àti lówó tó ni aṣọ tí wọn yóò fi sin òkú yóò ṣe pọ̀ tó. #AsoEbi #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ológìní dúró tandi, kò mira, ó na ìbọn rẹ̀ sí lákátabú, ò sì yín níbọn. Nígbà tí ọta ìbọn bàá lákínyẹmí ara, inú bí ẹrin... #itan #oremeji
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Kí a tó máa lọ, Ọ̀gbẹ́ni kan tí wọ́n ń pè ní Alájì ní wọn ò dá ẹnikẹ́ni lóhùn mọ́, kí àwọn èèyàn ó padà níjọ́ kẹta, ìyẹn àná.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Mo ki gbo gbo awa omo Karo Oji ri, ki apejo #TweetYoruba ko san wa si ire, owo, omo, alafia. Ki afefe ife, afefe ayo o fe s…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Irú kí ni gbogbo pálapàla réderède ráunràun yìí kẹ̀ ẹ? Ṣé ó yẹ kí a máa ṣera wa báyìí? Ọmọ ìyá kannáà fa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
iwo omo yi yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ṣeun tí ẹ fi iṣẹ́ yín ránṣẹ́ o. Àá wálé wá dúpẹ́ o. A ò ní m'ólè dání. 😁 Ẹ kú ojú lọ́nà ìkéde olùgbégbá orókè. #AtelewoPrize #Yoruba #Atelewo #kopoke https://t.co/9e32JeMY1O
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""Owo ti mo fẹẹ gba lọwọ salawa Abẹni lo koba mi"""""""" @user https://t.co/Umcjcfgd1Q https://t.co/gZikyea1Mw
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bi o se wu Oluwa ni nse Ola! http://t.co/n9j2bKw0oT
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ọdún tuntun oooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Saudi ni olú-ilẹ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí, Rome ni ti Àgùdà (catholic), England ni ti Anglican. Ifẹ̀ Oòdáyé ni ti wa. https://t.co/nMAY6wutbM
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìjẹ̀bú communities lagos mọ́lájoyè kétu odò ẹ̀gírí ìrayè òdómọ́lá imòkùn odò gbọ́nlé odò ṣíwọnlóyè tẹ̀mù ìrágùṣì igbó ńlá ìjì jégbéndé ògùn ìjẹ̀bú igbó ìjẹ̀bú òde imodi ìjàsí odò lẹ́mọ odò rẹ́mọ ìmàkà odògbólú atan ìláàdó mámu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user _proverbs: Ẹni má a mú ọ̀bọ á ṣe bí ọ̀bọ. / Whoever wants to catch a monkey would have to act like one. #yoruba…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwa niyen o, eku isé, eku gbigbe ede ati àsà laruge @user: Daadaa la wa, a dupe l'owo elduda fun ore ati anu re. E kaabo sori
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a kàn ń fi ayé ni ira wa lára ṣá ṣé mi ò ní kó lọ sí báyìí
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oto ni nan e gbe se tafin ko eko ni sin ko da bi tele toh oluwa yi o toju omo awa oluko yi nan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo nǹkan ni ó lẹ́wà, ṣùgbọ́n kìí ṣe gbogbo èèyàn ni ó lè rí i"""" - Confucius #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/Z1SyGoMFUv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ yorùbá oní ìsọkúsọ 😅😂😂👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding… https://t.co/JWD5rxemXW
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Sọ àwọn ọ̀rọ̀ ní Yorùbá (pronounce words in Yorùbá Wedding/marriage- ìgbéyàwó Wedding gown- aṣọ ìgbéyàwó Groom and bride-…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọpẹ́lọpẹ́ẹ Radio Abẹ́òkuta. Àwọn ni wọ́n gbée jáde fún wa. Ilé iṣẹ́ wọn ò ní jónán o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
word of the day ọ̀rọ̀ ọjọ́ òní ìbùbá kí a farapamọ́ kó ìjà òjijì bá èèyànẹranko ǹkan ìdí nì ìyẹn tí wọ́n fi ma ń sọ wípé a kìí bá ẹkùn ní ìbùbá gẹ̀ẹ́sì rẹ̀ ni ambushto attack someone from a concealed position you dont ambush a tiger
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
️ yorùbá kọ́ lẹ kọ nínú túwìtì yìí o àmì àti sílébù ni a fi ń pe ọ̀rọ̀ ìyàtọ̀ nìyẹn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọkàn sẹlẹ̀ wípé àwọn ọmọkùnrin tó dá aláwo dúdú ni wọn bẹ́ẹ̀ni àwọn ọmọkùnrin tí kò dá aláwò funfun ni wọ́n
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ̀wá wo bí agbèrò ṣe fọ́ kọ̀ndọ́ kan lójú l'Óṣòdí t'ẹ́jẹ̀ ń dà ṣuuruṣu nítorí ìyẹn ò fún un lówó oríta. @user @user #lagos
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìlú ẹkùnòsì lẹ́hìn tí wọ́n bí ifá ohun tí ó fa àrùn náà ifá fi yé wọn wípé àrùn tó ń dà wọ́n láàmú ọ̀yọ́ tí wọ́n kọ̀ tí wọ́n kò lọ mọ́ ló fàá láti dẹ́kun àrùn náà àfi kí wọ́n gbéra lọ sí ọ̀yọ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ èèyàn pẹ̀lú ọba àti baálẹ̀ ẹkùnòsì
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tí igi bá ré lu igi ti òkè rẹ la ńkọkọ gbé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á s'íbí, ìlẹ̀kẹ̀ má jà á s'ọ́ọ̀ún, ibi kan ló ma pàpà já sí. #OweYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yàtọ̀ fún gẹ̀ẹ́sì àti yorùbá àwọn èdè wo ni àwọn ọmọ naija ń sọ lórí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí kò bá sí ẹ̀sìn ìlú, kí wá lódé tí a ò fi dá ọdún ìbílẹ̀ mọ̀n bí ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá méjèèjì. @user #IseseHoliday #IseseLagba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Tí ẹ̀dá bá mọ iṣẹ́ àṣelà ni, ìwọ̀nba ni làálàá máa mọ. / If a man knows his destined path to success for sure, he will…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àti rí̀ Richard Mofe-Damijo (RMD) tó kó ipa Ejiro, ọmọ ìta tó ti fèyìntì fún ọ̀gá ọ̀daràn yàtọ̀ sí ipa tó máa ń kó tẹ́lẹ̀ bíi bàbá olówó. Ó sì ṣe dáadáa.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àwín ti jáde o, ẹ lọ ra ti yín. Onímúrí méjì àbọ̀ tí ọ̀rẹ́ mi rà fún mi ńbiṣẹ́ rè é. Aṣaralóore ni, ẹ lá a. #Yoruba https://t.co/CgCp194opu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bọ́tà (butter) kì í ṣe oúnjẹ ọ̀bọ. Ta l'ó kọ́kọ́ p'òwe ìgbàlódée nì gan-an! Mo mọ́ ọn ń rò, kílonítọ̀hún rí tí ó fi pa á. #Owe #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aaku Ojumo ooo dede omo alare... A ju eni se ne ni ooo. #yoruba #ijebu #babaijebu #faaji
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Omoluabi Iwa Ife Suuru #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: E kaaaro o. Emi ke? Bawo la se pin itan elede kan Lemoomu o? RT @user: @user Ẹ ... http://t.co/eXe204dJ7z
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èèyàn bíi ẹgbẹ̀rún lọ́nàa ẹgbẹ̀rún méjì ni ó gun òkè àràfá lónìí ní bí wọ́n bá sì ńbọ̀ nílẹ̀ ni wọ́n yóò pa ẹran
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user hmm,owo,aje,oniso iboji,oran towo dasile,apa owo konii ka.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ni odun ni ileise telefisan cnn bosi ori ero ayelujara cnn joins the internet
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""Ìyà mẹ́ta: O ò ní ìwà, o ò rẹwà, o ò tún lówó lọ́wọ́, ṣùgbọ́n o ní ìgbéraga!"""""""" - #Olahakeemola |#EdeYorubaDunLeti What…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gbogbo èèyàn oníwà tútù kọ́ lonínúure. / It is not everyone with quiet disposition who is kind-natured. [Appearance c…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
wọ́n á ní ó korò bíi jogbo ewée jogbo nẹ́ẹ̀ rè é o fún egbògi arànan mùjẹ̀mùjẹ̀ inú
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
5• Kíni DRAGON FLY lédè Yorùbá? #Ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user a le ni orile ede to wa losusu owo abi, orile ede ti won se ra won l'okan @user #MotherTongue
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀yin wà nípò ńlá ẹ fẹ́ fi bayé jẹ́ ẹ wà nípò ẹ̀yẹ ẹ fẹ́ sọ ọ́ di ti rírẹ́nijẹ ọ̀bàyéjẹ́ ni yín ìkà ni yín ọlọ́sà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user Iro patapata gba ni eyi ti e wi yi. E fe lu wa ni jibiti l…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òkú olówó oṣù mẹ́ta Òkú òtòṣì oṣù mẹ́fà Òkú ọlọ́mọ, àṣeeṣètán ni #okusinsin #yoruba #oroyoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Á wá jẹ́ pé kìí ṣe ará oko bíi tiwa yìí nìkan ló nsọ èdè Yoòbá. Njẹ́ ẹ rò pé ó ṣeéṣe bí?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó ku ọjọ́ mẹ́jọ fi iṣẹ́ rẹ ránṣẹ́ sí wa wo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìbànújẹ́! ìtìjú! Ìtìjú didan.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Kábíyèsí làá kí ọba Kára ó le làá kí ìjòyè Sáákì làá kí Ọmọba Kings are greeted: Kábíyèsí. Chiefs are greeted: Kára ó le (may you be healthy). Prince/Princess is greeted: Sáákì
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo ènìyàn ló fẹ́ ṣe ohun tí wọn ò tó ọmọdé fẹ́ gun ọkọ̀ bọ̀gìnì tí ẹgbẹ́ bàba rẹ̀ ò gùn torí àfihàn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train