| file_name,transcription
|
| wavs/yorubatts_00000.wav,"Jọ̀ọ́, dòmi"
|
| wavs/yorubatts_00001.wav,Mo ní ko kawé
|
| wavs/yorubatts_00002.wav,Ẹ̀ ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00003.wav,Wọ́n ṣiṣẹ́ gidigidi
|
| wavs/yorubatts_00004.wav,Ó máa ń jẹun ní òwúrọ̀.
|
| wavs/yorubatts_00005.wav,Awon iwé yẹn
|
| wavs/yorubatts_00006.wav,ìtàn
|
| wavs/yorubatts_00007.wav,Ó ń sùn nígbà tí mo de
|
| wavs/yorubatts_00008.wav,Èló ni bàtà naa?
|
| wavs/yorubatts_00009.wav,Ó yẹ kẹ yára lọ
|
| wavs/yorubatts_00010.wav,Óun ni
|
| wavs/yorubatts_00011.wav,Oun kọ́ ni olùkó
|
| wavs/yorubatts_00012.wav,gẹ́gẹ́ bó ti wù ú
|
| wavs/yorubatts_00013.wav,A máa ṣiṣẹ́ lọ́la
|
| wavs/yorubatts_00014.wav,Ilé rẹ
|
| wavs/yorubatts_00015.wav,Mo máa ń rerin nigbagbogbo
|
| wavs/yorubatts_00016.wav,bóyá
|
| wavs/yorubatts_00017.wav,àti
|
| wavs/yorubatts_00018.wav,Ilé ńlá
|
| wavs/yorubatts_00019.wav,Mo fẹ́ kòkò sinmi
|
| wavs/yorubatts_00020.wav,Ó ra kẹ̀kẹ́ látí máa gùn lọ sí ilé ẹ̀kọ́
|
| wavs/yorubatts_00021.wav,Wọ́n ti lọ
|
| wavs/yorubatts_00022.wav,O ò jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́
|
| wavs/yorubatts_00023.wav,Kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00024.wav,Wọ́n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00025.wav,Àwa ni
|
| wavs/yorubatts_00026.wav,A ò jẹ́ oníṣòwò
|
| wavs/yorubatts_00027.wav,Mo fẹ́ lọ sí ilé eko
|
| wavs/yorubatts_00028.wav,òru
|
| wavs/yorubatts_00029.wav,bàtà
|
| wavs/yorubatts_00030.wav,Mà jẹun!
|
| wavs/yorubatts_00031.wav,A duro títí di òwúrọ̀
|
| wavs/yorubatts_00032.wav,Ṣé o mọ̀ bí a ṣe...?
|
| wavs/yorubatts_00033.wav,pàdé
|
| wavs/yorubatts_00034.wav,jínnà sí
|
| wavs/yorubatts_00035.wav,legbee
|
| wavs/yorubatts_00036.wav,Kò sí níbẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00037.wav,"To bá ti dáhùn, m ba ti mọ nkan to fẹ́"
|
| wavs/yorubatts_00038.wav,Obìnrin kùkùrù
|
| wavs/yorubatts_00039.wav,Ẹ̀ ò ní ta a
|
| wavs/yorubatts_00040.wav,David bí mí bóyá mo ní owó
|
| wavs/yorubatts_00041.wav,Àgọ́ mẹ́ta ni
|
| wavs/yorubatts_00042.wav,ṣùgbọ́n
|
| wavs/yorubatts_00043.wav,Eyin lo jẹ́ ẹ
|
| wavs/yorubatts_00044.wav,Ó yẹ kí n lọ sí ilé ìwòsàn
|
| wavs/yorubatts_00045.wav,"Tó bá ti rá oyin, a ba ti fi sí ounje wa"
|
| wavs/yorubatts_00046.wav,Èmi ni
|
| wavs/yorubatts_00047.wav,Mo ṣiṣẹ́ kí n lè ṣàṣeyọrí
|
| wavs/yorubatts_00048.wav,Báwo ni?
|
| wavs/yorubatts_00049.wav,Kí n tó jẹun
|
| wavs/yorubatts_00050.wav,Ó ń wá gẹ́gẹ́ bó ti wù ú
|
| wavs/yorubatts_00051.wav,Mo ti de
|
| wavs/yorubatts_00052.wav,Ó n bẹ̀rù
|
| wavs/yorubatts_00053.wav,Èwo lo fẹ́?
|
| wavs/yorubatts_00054.wav,"Tó bá ti ràn mí lọ́wọ́, m ba ti parí bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00055.wav,Wọ́n ò ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00056.wav,Wọ́n ní ka máa bọ̀
|
| wavs/yorubatts_00057.wav,Ẹ kúrọ̀lẹ́
|
| wavs/yorubatts_00058.wav,Àwa la sare
|
| wavs/yorubatts_00059.wav,Iru mọtọ̀ wo ló ní?
|
| wavs/yorubatts_00060.wav,David máa ń lo si London ni ọ̀sẹ̀ kookan
|
| wavs/yorubatts_00061.wav,Ẹ̀ ò ti sètán
|
| wavs/yorubatts_00062.wav,Wọ́n ò ti sètán
|
| wavs/yorubatts_00063.wav,tà
|
| wavs/yorubatts_00064.wav,Àpò naa
|
| wavs/yorubatts_00065.wav,mẹje
|
| wavs/yorubatts_00066.wav,ìfẹ̀kúfẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00067.wav,Ó yẹ ko mu omi púpọ̀
|
| wavs/yorubatts_00068.wav,lẹ̀yìn
|
| wavs/yorubatts_00069.wav,mu
|
| wavs/yorubatts_00070.wav,O ò ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00071.wav,Àwọn ni
|
| wavs/yorubatts_00072.wav,se
|
| wavs/yorubatts_00073.wav,"Ta bá lọ, a ò ní pẹ̀ padà"
|
| wavs/yorubatts_00074.wav,Ó rò pé a kò ní lọ síbi yẹn.
|
| wavs/yorubatts_00075.wav,"Ta bá ti ṣiṣẹ́, a ba ti gba owó"
|
| wavs/yorubatts_00076.wav,A n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00077.wav,Mo maa wa
|
| wavs/yorubatts_00078.wav,Wọ́n ò rẹ́rìn
|
| wavs/yorubatts_00079.wav,A ò jẹun
|
| wavs/yorubatts_00080.wav,O kì í jẹ iresi
|
| wavs/yorubatts_00081.wav,Mo máa ń lọ sí ilé ẹ̀kọ́ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan
|
| wavs/yorubatts_00082.wav,À kì í ṣe oníṣòwò
|
| wavs/yorubatts_00083.wav,Ọkùnrin tó n ṣiṣẹ́
|
| wavs/yorubatts_00084.wav,"Tẹ bá ti fi tọ́kàntọ́kàn ṣiṣẹ́, ẹ̀ ba ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wa bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00085.wav,Ẹ̀yin
|
| wavs/yorubatts_00086.wav,"Tí wọ́n bá ti ṣiṣẹ́, wọ́n bá ti gba owó"
|
| wavs/yorubatts_00087.wav,James fẹ́ ki n má lọ
|
| wavs/yorubatts_00088.wav,Mo gbọ́dọ̀
|
| wavs/yorubatts_00089.wav,gbígbóná
|
| wavs/yorubatts_00090.wav,"Nígbà naa, ó ń jẹun"
|
| wavs/yorubatts_00091.wav,títí di
|
| wavs/yorubatts_00092.wav,Mo maa lọ
|
| wavs/yorubatts_00093.wav,Mo ní láti
|
| wavs/yorubatts_00094.wav,"Ti David bá ti yára, o ba ti wà lọjà bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00095.wav,"Tó bá ti dé, a ò ba ni ronu"
|
| wavs/yorubatts_00096.wav,Ó yẹ ko kòkò jẹun
|
| wavs/yorubatts_00097.wav,Ó gbà pé a kò ní lọ síbi yẹn.
|
| wavs/yorubatts_00098.wav,bí
|
| wavs/yorubatts_00099.wav,tóbi
|
| wavs/yorubatts_00100.wav,"Tí wọ́n bá ti bẹ̀rẹ̀ ní kutukutu, wọ́n ba ti parí iṣẹ́"
|
| wavs/yorubatts_00101.wav,Ó jẹun
|
| wavs/yorubatts_00102.wav,Mo n bo
|
| wavs/yorubatts_00103.wav,Iru ilé wo ni yẹn?
|
| wavs/yorubatts_00104.wav,Wọ́n sọ pé wọn ti dé.
|
| wavs/yorubatts_00105.wav,Mo maa jade
|
| wavs/yorubatts_00106.wav,Kò ti sètán
|
| wavs/yorubatts_00107.wav,Mo sọ pé ka má ṣiṣẹ́
|
| wavs/yorubatts_00108.wav,Mo n je iresi
|
| wavs/yorubatts_00109.wav,Mo máa ṣiṣẹ́ laalẹ́
|
| wavs/yorubatts_00110.wav,Otutu n mu mi
|
| wavs/yorubatts_00111.wav,Ẹ̀ ra a
|
| wavs/yorubatts_00112.wav,Má jẹ́ kí n lọ
|
| wavs/yorubatts_00113.wav,"O máa lọ, àbí?"
|
| wavs/yorubatts_00114.wav,A máa jẹun
|
| wavs/yorubatts_00115.wav,Awa kọ̀ ló béèrè
|
| wavs/yorubatts_00116.wav,Ẹ̀yin n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00117.wav,Mi o fẹ́ ko lọ
|
| wavs/yorubatts_00118.wav,Ẹ dín owó síi
|
| wavs/yorubatts_00119.wav,Wọ́n tẹ́tẹ́ dá a lóhùn
|
| wavs/yorubatts_00120.wav,Ó wọ ilé gbé apótí jáde
|
| wavs/yorubatts_00121.wav,Mo rí wọn
|
| wavs/yorubatts_00122.wav,Iwo tabi emi?
|
| wavs/yorubatts_00123.wav,A yá owó látí ra ohun èlò
|
| wavs/yorubatts_00124.wav,ìfẹ́
|
| wavs/yorubatts_00125.wav,wọn
|
| wavs/yorubatts_00126.wav,Wọ́n lọ sí ibudo látí rí aláìlera
|
| wavs/yorubatts_00127.wav,Bá mi ṣe ìṣe naa
|
| wavs/yorubatts_00128.wav,Mo gbọ́ pé ó fẹ́ràn rẹ.
|
| wavs/yorubatts_00129.wav,Mo lè
|
| wavs/yorubatts_00130.wav,ìfarapa
|
| wavs/yorubatts_00131.wav,pẹ̀lú ìtìjú
|
| wavs/yorubatts_00132.wav,Wọ́n ò kùrù
|
| wavs/yorubatts_00133.wav,A ní moto
|
| wavs/yorubatts_00134.wav,èyí ni ìdí tí
|
| wavs/yorubatts_00135.wav,baba
|
| wavs/yorubatts_00136.wav,Obìnrin tó kéré
|
| wavs/yorubatts_00137.wav,Èmi lo lọ
|
| wavs/yorubatts_00138.wav,"Ó rẹ̀, nítorí náà ó sùn"
|
| wavs/yorubatts_00139.wav,Mo le bá ọ ṣe
|
| wavs/yorubatts_00140.wav,ìrírí
|
| wavs/yorubatts_00141.wav,O re mi
|
| wavs/yorubatts_00142.wav,Ẹ̀ máa se òbẹ
|
| wavs/yorubatts_00143.wav,lábe
|
| wavs/yorubatts_00144.wav,Wọ́n máa se òbẹ
|
| wavs/yorubatts_00145.wav,mẹ́fà
|
| wavs/yorubatts_00146.wav,láì sí
|
| wavs/yorubatts_00147.wav,Ko sí eran níbí
|
| wavs/yorubatts_00148.wav,"Ta ò bá mura, a ò ní ṣàṣeyọrí"
|
| wavs/yorubatts_00149.wav,Mo ti lọ ra ìwé
|
| wavs/yorubatts_00150.wav,Ṣé o fẹ́ kí n bá ẹ ra omi?
|
| wavs/yorubatts_00151.wav,Kò rẹ́rìn
|
| wavs/yorubatts_00152.wav,Ó ra a
|
| wavs/yorubatts_00153.wav,Ó mọ̀ bí a ṣe ń kọrin
|
| wavs/yorubatts_00154.wav,Emi nko?
|
| wavs/yorubatts_00155.wav,Ṣé wọ́n le bá mi ra ounjẹ?
|
| wavs/yorubatts_00156.wav,"Tí m bá ní owó, mo màá rà moto"
|
| wavs/yorubatts_00157.wav,Otutu
|
| wavs/yorubatts_00158.wav,Mi ò mọ̀
|
| wavs/yorubatts_00159.wav,Ó rí mi
|
| wavs/yorubatts_00160.wav,tó jẹ́ pé
|
| wavs/yorubatts_00161.wav,Óun lo sá
|
| wavs/yorubatts_00162.wav,A ò rẹ́rìn
|
| wavs/yorubatts_00163.wav,"Tí won bá ti bí mi ní àkókò yẹn, mi ò ní lọ si ilé-ẹ̀kọ́"
|
| wavs/yorubatts_00164.wav,Èmi
|
| wavs/yorubatts_00165.wav,À kì í gba bọ́ọ̀lù
|
| wavs/yorubatts_00166.wav,Mo ní ìfẹ́ rẹ
|
| wavs/yorubatts_00167.wav,Ó kì í gboran
|
| wavs/yorubatts_00168.wav,Mo n jeun bayii
|
| wavs/yorubatts_00169.wav,ìforúkọsílẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00170.wav,Mo lọ ra omi
|
| wavs/yorubatts_00171.wav,Iru aṣọ wo ló máa ń wọ̀?
|
| wavs/yorubatts_00172.wav,Wọ́n máa jẹun
|
| wavs/yorubatts_00173.wav,Lẹ́yìn tí
|
| wavs/yorubatts_00174.wav,À se oúnjẹ láì niyọ̀
|
| wavs/yorubatts_00175.wav,A ò mọ̀ bí a ṣe ń ṣe é
|
| wavs/yorubatts_00176.wav,"A máa dé, o dájú"
|
| wavs/yorubatts_00177.wav,Ó ṣiṣẹ́ dáadáa tó jẹ́ pé gbogbo ènìyàn yìn ín
|
| wavs/yorubatts_00178.wav,ṣe
|
| wavs/yorubatts_00179.wav,O ṣéé ṣé
|
| wavs/yorubatts_00180.wav,A lọ kàwé
|
| wavs/yorubatts_00181.wav,Ó lọ làná
|
| wavs/yorubatts_00182.wav,Ka tó sọ̀rọ̀
|
| wavs/yorubatts_00183.wav,Èwo ni ilé rẹ?
|
| wavs/yorubatts_00184.wav,Jẹun!
|
| wavs/yorubatts_00185.wav,"Ta bá ti yára, a ba ti wà lọjà bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00186.wav,A ra a
|
| wavs/yorubatts_00187.wav,rà
|
| wavs/yorubatts_00188.wav,Mo kùrù
|
| wavs/yorubatts_00189.wav,Mi ò rẹ́rìn
|
| wavs/yorubatts_00190.wav,"Te ba ra moto, e pe mi fun ayeye"
|
| wavs/yorubatts_00191.wav,Kí ni ìṣòro náà?
|
| wavs/yorubatts_00192.wav,Mo máa ń lọ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan
|
| wavs/yorubatts_00193.wav,Lẹ́yìn náà
|
| wavs/yorubatts_00194.wav,àtijọ́
|
| wavs/yorubatts_00195.wav,"Tí m bá ti ṣiṣẹ́, m ba ti ní owó bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00196.wav,Mo ra aṣọ nítorí pé mo ní owó
|
| wavs/yorubatts_00197.wav,Mo gbàdúrà ka má ṣe aṣìṣe
|
| wavs/yorubatts_00198.wav,Ó wà ní ilé
|
| wavs/yorubatts_00199.wav,èrè
|
| wavs/yorubatts_00200.wav,Ó jẹ́ ìrírí ayọ̀ fún mi
|
| wavs/yorubatts_00201.wav,ni ìdákẹ́jẹ
|
| wavs/yorubatts_00202.wav,O ṣéé ṣé kí n le ra
|
| wavs/yorubatts_00203.wav,Ó máa ń jẹun lojoojumo
|
| wavs/yorubatts_00204.wav,Mo sọ fún un kó má ṣe é mọ́
|
| wavs/yorubatts_00205.wav,A ò ti sètán
|
| wavs/yorubatts_00206.wav,wá
|
| wavs/yorubatts_00207.wav,lojoojumo
|
| wavs/yorubatts_00208.wav,Mo lọ mu omi
|
| wavs/yorubatts_00209.wav,gbe
|
| wavs/yorubatts_00210.wav,Ó sáré bí ẹni tí olopaa ń lé
|
| wavs/yorubatts_00211.wav,David ni iba
|
| wavs/yorubatts_00212.wav,Ọmọ tó dáa
|
| wavs/yorubatts_00213.wav,"Ta bá ti ṣiṣẹ́, a ba ti gba owó"
|
| wavs/yorubatts_00214.wav,Èmi kọ́ ni olùkó
|
| wavs/yorubatts_00215.wav,ṣùgbọ́n
|
| wavs/yorubatts_00216.wav,Ẹ kú ọdún
|
| wavs/yorubatts_00217.wav,A gbàdúrà kí wọ́n lè ṣàṣeyọrí
|
| wavs/yorubatts_00218.wav,Mi ò jẹ́ olùkó
|
| wavs/yorubatts_00219.wav,Mo máa jẹun
|
| wavs/yorubatts_00220.wav,Mo ti lọ
|
| wavs/yorubatts_00221.wav,Ó wí pé a kò ní lọ síbi yẹn.
|
| wavs/yorubatts_00222.wav,Ó ń bínú
|
| wavs/yorubatts_00223.wav,"Tí mi ò bá ti lọ, mi o ba ní rí i"
|
| wavs/yorubatts_00224.wav,Ìwọ lo bẹ̀rẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00225.wav,A ti lọ
|
| wavs/yorubatts_00226.wav,Mo béèrè bóyá ó ti lọ
|
| wavs/yorubatts_00227.wav,Ó ní kí n lọ
|
| wavs/yorubatts_00228.wav,Má jẹ́ kí ó jẹun
|
| wavs/yorubatts_00229.wav,"Mo ní owó, nítorí náà mo ra aṣọ"
|
| wavs/yorubatts_00230.wav,Tẹ́tẹ́ dá a lóhùn
|
| wavs/yorubatts_00231.wav,Inu mi ń dun mí
|
| wavs/yorubatts_00232.wav,Mo lọ sí ọjà pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi
|
| wavs/yorubatts_00233.wav,súnmo
|
| wavs/yorubatts_00234.wav,Ẹ̀yin kọ̀
|
| wavs/yorubatts_00235.wav,Kò yẹ kó ṣiṣẹ́ lónìí
|
| wavs/yorubatts_00236.wav,Ó sọ̀rọ̀ ni ìdákẹ́jẹ
|
| wavs/yorubatts_00237.wav,Ọwọ́
|
| wavs/yorubatts_00238.wav,"To ba je àwọn, wọ́n ò ní yá owó"
|
| wavs/yorubatts_00239.wav,pẹ̀lú ibinnu
|
| wavs/yorubatts_00240.wav,Mi ò jẹun
|
| wavs/yorubatts_00241.wav,Ó yẹ kó sinmi
|
| wavs/yorubatts_00242.wav,Àwa
|
| wavs/yorubatts_00243.wav,Àwa fẹ́ kí wọ́n bọ̀ láàyè
|
| wavs/yorubatts_00244.wav,Ẹran wà níbẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00245.wav,Mo fẹ́ràn èso bí ògẹ̀dẹ̀ àti ọ̀sán
|
| wavs/yorubatts_00246.wav,mẹ́ta
|
| wavs/yorubatts_00247.wav,Ó ní kí wọn má pariwo
|
| wavs/yorubatts_00248.wav,Ọmọ ọdún mélòó ni ọ?
|
| wavs/yorubatts_00249.wav,Ó mọ̀ bí won ṣe ṣé
|
| wavs/yorubatts_00250.wav,je
|
| wavs/yorubatts_00251.wav,Kò gbọ́ rárá
|
| wavs/yorubatts_00252.wav,Ó lọ láì kí ẹnikẹ́ni
|
| wavs/yorubatts_00253.wav,gan-an
|
| wavs/yorubatts_00254.wav,Etí
|
| wavs/yorubatts_00255.wav,"Nígbà naa, ó ń jẹun"
|
| wavs/yorubatts_00256.wav,pupo
|
| wavs/yorubatts_00257.wav,Báwo ni mo ṣe le ràn ẹ́ lọwọ?
|
| wavs/yorubatts_00258.wav,ọmọ
|
| wavs/yorubatts_00259.wav,Ẹ̀ ò ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00260.wav,Kó tó sùn
|
| wavs/yorubatts_00261.wav,kíákíá
|
| wavs/yorubatts_00262.wav,ọ̀kan
|
| wavs/yorubatts_00263.wav,Wọ́n máa jẹun ni ọ̀sán
|
| wavs/yorubatts_00264.wav,O ò ní ta a
|
| wavs/yorubatts_00265.wav,O jẹun
|
| wavs/yorubatts_00266.wav,Àgọ́ mélòó lo lu?
|
| wavs/yorubatts_00267.wav,O kì í ṣe akẹ́kọ̀ọ́
|
| wavs/yorubatts_00268.wav,O ra a
|
| wavs/yorubatts_00269.wav,A bẹ̀rẹ̀ látí kọ́ ìtàn Yorùbá
|
| wavs/yorubatts_00270.wav,ajọyọ̀
|
| wavs/yorubatts_00271.wav,Ṣé wọ́n mọ̀ bí a ṣe ń taja?
|
| wavs/yorubatts_00272.wav,À ò burú
|
| wavs/yorubatts_00273.wav,àti
|
| wavs/yorubatts_00274.wav,"Tójo bá rọ̀, mi ò ní lọ"
|
| wavs/yorubatts_00275.wav,Kí ni wọ́n fẹ́?
|
| wavs/yorubatts_00276.wav,Báwo lo ṣe fẹ́?
|
| wavs/yorubatts_00277.wav,A máa se òbẹ
|
| wavs/yorubatts_00278.wav,David lo jẹ́ ẹ
|
| wavs/yorubatts_00279.wav,ayọ̀
|
| wavs/yorubatts_00280.wav,"To bá ti wá, a ò bá ní ronu"
|
| wavs/yorubatts_00281.wav,Ó sáré ra ewé
|
| wavs/yorubatts_00282.wav,Èmi n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00283.wav,Ṣé ó wà ní ilé?
|
| wavs/yorubatts_00284.wav,Ṣe ìse amurele rẹ!
|
| wavs/yorubatts_00285.wav,Mo fẹ́ kó ṣàseyọrí
|
| wavs/yorubatts_00286.wav,A ò ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00287.wav,Kò ṣéé ṣé
|
| wavs/yorubatts_00288.wav,Ta lo ṣe yen?
|
| wavs/yorubatts_00289.wav,Báwo lo ṣe ṣe?
|
| wavs/yorubatts_00290.wav,O ò ti sètán
|
| wavs/yorubatts_00291.wav,Inú mi bàjẹ́
|
| wavs/yorubatts_00292.wav,Mi ò ní jẹun
|
| wavs/yorubatts_00293.wav,Inú rẹ bàjẹ́
|
| wavs/yorubatts_00294.wav,Ẹ káàrọ̀
|
| wavs/yorubatts_00295.wav,"Tele, mo máa ń sáré lojoojúmọ́"
|
| wavs/yorubatts_00296.wav,kéré
|
| wavs/yorubatts_00297.wav,"Tí m bá ti kàwé, m ba ti yẹ́gé"
|
| wavs/yorubatts_00298.wav,ìlú
|
| wavs/yorubatts_00299.wav,O rin pelu ibinnu
|
| wavs/yorubatts_00300.wav,Ọri n fo mi
|
| wavs/yorubatts_00301.wav,O ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00302.wav,ẹnu
|
| wavs/yorubatts_00303.wav,Mo mọ̀ bí ó ṣe ṣe
|
| wavs/yorubatts_00304.wav,Ìwọ
|
| wavs/yorubatts_00305.wav,Ọmọkùnrin gíga
|
| wavs/yorubatts_00306.wav,Mo joko pelu Jane
|
| wavs/yorubatts_00307.wav,Mo ga
|
| wavs/yorubatts_00308.wav,Mo fẹ́
|
| wavs/yorubatts_00309.wav,Ìtàn náà bà mí nínú
|
| wavs/yorubatts_00310.wav,Ṣé o fẹ́ lọ?
|
| wavs/yorubatts_00311.wav,Bàtà yìí
|
| wavs/yorubatts_00312.wav,gbà
|
| wavs/yorubatts_00313.wav,"Ta bá ṣiṣẹ́, a máa rí èrè"
|
| wavs/yorubatts_00314.wav,marún
|
| wavs/yorubatts_00315.wav,àlàáfíà
|
| wavs/yorubatts_00316.wav,Ẹ Jẹun!
|
| wavs/yorubatts_00317.wav,Ó kawé kó lè yẹ́gé ní ìdánwò
|
| wavs/yorubatts_00318.wav,àjálù
|
| wavs/yorubatts_00319.wav,Ó n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00320.wav,síi
|
| wavs/yorubatts_00321.wav,Inú wa dùn gan-an
|
| wavs/yorubatts_00322.wav,ṣáájú
|
| wavs/yorubatts_00323.wav,Ó wà níbí
|
| wavs/yorubatts_00324.wav,Ó gbàdúrà kí ìyàwó rẹ̀ rí àlàáfíà
|
| wavs/yorubatts_00325.wav,"Nítorí pé mo ní owó, mo ra aṣọ"
|
| wavs/yorubatts_00326.wav,Mo lọ ra ìwé
|
| wavs/yorubatts_00327.wav,kòkò
|
| wavs/yorubatts_00328.wav,Kò ní jẹun
|
| wavs/yorubatts_00329.wav,"Mo fẹ́ lọ, ṣùgbọ́n mi ò ní owó"
|
| wavs/yorubatts_00330.wav,"To ba ni owó, mi o ni be o"
|
| wavs/yorubatts_00331.wav,Nigbà wo lo máa lọ?
|
| wavs/yorubatts_00332.wav,Ṣé wọ́n lè ṣiṣẹ́?
|
| wavs/yorubatts_00333.wav,nítorí pé
|
| wavs/yorubatts_00334.wav,Mo ní kí wọn má bá wa wí
|
| wavs/yorubatts_00335.wav,Ó ti lọ ni ojo meji to koja
|
| wavs/yorubatts_00336.wav,mẹ́sán
|
| wavs/yorubatts_00337.wav,Má jẹ́ kó jẹun
|
| wavs/yorubatts_00338.wav,ìtùnú
|
| wavs/yorubatts_00339.wav,Kí ló dé?
|
| wavs/yorubatts_00340.wav,Ó wá rà ọkọ̀
|
| wavs/yorubatts_00341.wav,"Tí m bá ní owó, mi ò ní fi sílẹ̀"
|
| wavs/yorubatts_00342.wav,"To ò bá ti wá, a ò bá ní bẹ̀rù"
|
| wavs/yorubatts_00343.wav,Mo ra a
|
| wavs/yorubatts_00344.wav,À ò tobi
|
| wavs/yorubatts_00345.wav,kùkùrù
|
| wavs/yorubatts_00346.wav,A ò ní ta a
|
| wavs/yorubatts_00347.wav,Èmi ni olùkọ́
|
| wavs/yorubatts_00348.wav,Kò ṣéé ṣé kó ṣẹlẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00349.wav,Mo n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00350.wav,Wọ́n máa wá ni òwúrọ̀
|
| wavs/yorubatts_00351.wav,Ó le bá mi ṣiṣẹ́
|
| wavs/yorubatts_00352.wav,Mo béèrè pé Ṣé ó ti lọ?
|
| wavs/yorubatts_00353.wav,kankan
|
| wavs/yorubatts_00354.wav,Wọ́n ò ní jẹun
|
| wavs/yorubatts_00355.wav,lórí
|
| wavs/yorubatts_00356.wav,"To ba je ìwọ , o ò ní jẹ́ kí wọ́n fẹ̀sùn kàn ọ"
|
| wavs/yorubatts_00357.wav,"Tí kò bá ti wá, a ò ba ní gbà á"
|
| wavs/yorubatts_00358.wav,A wọlé pẹ̀lú ìtìjú
|
| wavs/yorubatts_00359.wav,tuntun
|
| wavs/yorubatts_00360.wav,Mi ò ní ta a
|
| wavs/yorubatts_00361.wav,Ó tèlé wa
|
| wavs/yorubatts_00362.wav,ni ọ̀sẹ̀ kookan
|
| wavs/yorubatts_00363.wav,Mo fẹ́ kí wọn má wá síbí
|
| wavs/yorubatts_00364.wav,Bá mi ra moto naa
|
| wavs/yorubatts_00365.wav,Ìwé wà níbí
|
| wavs/yorubatts_00366.wav,Awọ́n kọ́ ni ọ̀lọ́́jọ́gbọ́n
|
| wavs/yorubatts_00367.wav,ìdílé
|
| wavs/yorubatts_00368.wav,"Jọ̀wọ́, kọ́ wa bí a ṣe ń sọ Yorùbá"
|
| wavs/yorubatts_00369.wav,Jẹ́ ko sùn
|
| wavs/yorubatts_00370.wav,O ò ní jẹun
|
| wavs/yorubatts_00371.wav,Ó wà níbẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00372.wav,Mo mọ̀ bí ó ṣe lè ṣe é
|
| wavs/yorubatts_00373.wav,Ẹ kaàbọ̀
|
| wavs/yorubatts_00374.wav,Mo mọ̀ bí wọ́n ṣe ṣé
|
| wavs/yorubatts_00375.wav,gẹ́gẹ́ bí
|
| wavs/yorubatts_00376.wav,Àgọ́ márùn kọja ìsẹ́jú mẹ́wà
|
| wavs/yorubatts_00377.wav,"Tí mi ò bá lọ, ó máa bínú"
|
| wavs/yorubatts_00378.wav,Mi kì í jẹ ewa
|
| wavs/yorubatts_00379.wav,"Tó bá ti kọ́ ẹ̀kọ́ dáadáa, ó ba ti mọ nkan tí wọ́n ń sọ"
|
| wavs/yorubatts_00380.wav,Ó sọ̀rọ̀ bí agbẹjọ́rò
|
| wavs/yorubatts_00381.wav,A ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00382.wav,"Lẹ́yìn tí mo jẹun, mo lọ sùn."
|
| wavs/yorubatts_00383.wav,"To bá lọ sí London, o máa gbádùn"
|
| wavs/yorubatts_00384.wav,Ó máa jẹun
|
| wavs/yorubatts_00385.wav,Ó dára jùlọ
|
| wavs/yorubatts_00386.wav,Ẹ n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00387.wav,Èmi kọ̀
|
| wavs/yorubatts_00388.wav,Mi ò ga
|
| wavs/yorubatts_00389.wav,Àṣọ yìí dára ju ti yẹn lọ
|
| wavs/yorubatts_00390.wav,ìtẹ́lọ́rùn
|
| wavs/yorubatts_00391.wav,Èyí ni ìdí tí mo fi lọ
|
| wavs/yorubatts_00392.wav,Iba
|
| wavs/yorubatts_00393.wav,Jẹun síi
|
| wavs/yorubatts_00394.wav,Inú
|
| wavs/yorubatts_00395.wav,pẹ̀lú
|
| wavs/yorubatts_00396.wav,A kòkò jẹun ka tó lọ
|
| wavs/yorubatts_00397.wav,Ó yẹ kí wọn tẹ́tẹ́ fi han
|
| wavs/yorubatts_00398.wav,Wọ́n ra a
|
| wavs/yorubatts_00399.wav,Mo mọ̀ bí a ṣe ń dana
|
| wavs/yorubatts_00400.wav,Òun n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00401.wav,tún
|
| wavs/yorubatts_00402.wav,"Tí wọ́n bá pe mi, mo màá wa"
|
| wavs/yorubatts_00403.wav,Obìnrin tó kùrù
|
| wavs/yorubatts_00404.wav,so
|
| wavs/yorubatts_00405.wav,Òun
|
| wavs/yorubatts_00406.wav,"Ta bá ti lọ sí ilé-ẹ̀kọ́, a ba ti gbọ́ ìtàn náà bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00407.wav,tẹ́tẹ́
|
| wavs/yorubatts_00408.wav,Bàtà mi
|
| wavs/yorubatts_00409.wav,Ó bí mí bóyá mo ní owó
|
| wavs/yorubatts_00410.wav,O máa jẹun
|
| wavs/yorubatts_00411.wav,A ń ṣiṣẹ́ nígbà náà
|
| wavs/yorubatts_00412.wav,àbí
|
| wavs/yorubatts_00413.wav,Tún Ṣe
|
| wavs/yorubatts_00414.wav,Wọ́n máa lọ ni odun to n bo
|
| wavs/yorubatts_00415.wav,Wọ́n lè ṣeré
|
| wavs/yorubatts_00416.wav,Mo fẹ́ pe ẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00417.wav,Ẹ káàsán
|
| wavs/yorubatts_00418.wav,Kò burú
|
| wavs/yorubatts_00419.wav,Ilé wa
|
| wavs/yorubatts_00420.wav,Ó ní ilé
|
| wavs/yorubatts_00421.wav,Mo sọ pé kí wọn má ṣiṣẹ́
|
| wavs/yorubatts_00422.wav,Wọ́n ò mọ̀ bí a ṣe ń kàwé
|
| wavs/yorubatts_00423.wav,Ìwọ ni
|
| wavs/yorubatts_00424.wav,"Nígbà tí mo dé, ó ń jẹun"
|
| wavs/yorubatts_00425.wav,Mi ò ní jẹun kankan
|
| wavs/yorubatts_00426.wav,"To bá ti wá, a ò ní bẹ̀rù"
|
| wavs/yorubatts_00427.wav,"To ò bá kawe, o ò ní yege"
|
| wavs/yorubatts_00428.wav,Inú mi dùn
|
| wavs/yorubatts_00429.wav,Ó gbagbo pé a kò ní lọ síbi yẹn.
|
| wavs/yorubatts_00430.wav,Ó maa ń ṣiṣẹ́ nigbagbogbo
|
| wavs/yorubatts_00431.wav,O ò rẹ́rìn
|
| wavs/yorubatts_00432.wav,O n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00433.wav,Kí ni orúkọ rẹ?
|
| wavs/yorubatts_00434.wav,mẹ́rin
|
| wavs/yorubatts_00435.wav,owó
|
| wavs/yorubatts_00436.wav,"Nítorí pé mo ní owó, mo ra aṣọ tuntun"
|
| wavs/yorubatts_00437.wav,Mo máa lọ ra oúnjẹ
|
| wavs/yorubatts_00438.wav,Ìyá àti Bàbá wà nílé
|
| wavs/yorubatts_00439.wav,A jẹun
|
| wavs/yorubatts_00440.wav,Ó máa se òbẹ
|
| wavs/yorubatts_00441.wav,Ó ò ní ṣiṣẹ́ mọ̀
|
| wavs/yorubatts_00442.wav,gíga
|
| wavs/yorubatts_00443.wav,Mo fẹ́ ko má lọ
|
| wavs/yorubatts_00444.wav,Mo le bà e ra omi
|
| wavs/yorubatts_00445.wav,Kọ́ mi bí a ṣe ń bù ọbẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00446.wav,Wọ́n mú ẹran jẹ
|
| wavs/yorubatts_00447.wav,Bàtà yìí kéré jùlọ
|
| wavs/yorubatts_00448.wav,ìṣòro
|
| wavs/yorubatts_00449.wav,mẹ́wà
|
| wavs/yorubatts_00450.wav,"To ò bá ti wá, a ò bá ní bẹ̀rù"
|
| wavs/yorubatts_00451.wav,Mo lọ ra ìwé
|
| wavs/yorubatts_00452.wav,Ilé yẹn
|
| wavs/yorubatts_00453.wav,Mo tobi
|
| wavs/yorubatts_00454.wav,burúkú
|
| wavs/yorubatts_00455.wav,Mo máa ń jeun gan-an nigba ti mo kere.
|
| wavs/yorubatts_00456.wav,rẹ́rìn músẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00457.wav,Àwa lọ rí bàbá wa
|
| wavs/yorubatts_00458.wav,Ó jẹ́ dollar marun
|
| wavs/yorubatts_00459.wav,Ó n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00460.wav,ogún
|
| wavs/yorubatts_00461.wav,Mo máa ń lọ sí ilé ẹ̀kọ́.
|
| wavs/yorubatts_00462.wav,Nígbà náà
|
| wavs/yorubatts_00463.wav,Ìrìnàjò náà dùn mo mi gan-an
|
| wavs/yorubatts_00464.wav,Oun lo béèrè
|
| wavs/yorubatts_00465.wav,Ẹ ò jẹ́ olórin
|
| wavs/yorubatts_00466.wav,ẹni
|
| wavs/yorubatts_00467.wav,Mo máa ṣiṣẹ́ laalẹ́
|
| wavs/yorubatts_00468.wav,Awon bàtà yìí
|
| wavs/yorubatts_00469.wav,Mo ní ìbànújẹ
|
| wavs/yorubatts_00470.wav,Ta lo wa níta?
|
| wavs/yorubatts_00471.wav,Níbo ni ilé rẹ?
|
| wavs/yorubatts_00472.wav,Ó gbọ́dọ̀ ṣiṣẹ́
|
| wavs/yorubatts_00473.wav,Bàtà wà níbẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00474.wav,Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́
|
| wavs/yorubatts_00475.wav,David kọ̀ ló wá
|
| wavs/yorubatts_00476.wav,Iru bàtà wo le rà?
|
| wavs/yorubatts_00477.wav,Mo ní ko kawé
|
| wavs/yorubatts_00478.wav,Bá mi kọ́wé
|
| wavs/yorubatts_00479.wav,Ẹ kúúṣẹ́
|
| wavs/yorubatts_00480.wav,Apá mi ń dun mi
|
| wavs/yorubatts_00481.wav,David ga ju James lọ
|
| wavs/yorubatts_00482.wav,níwájú
|
| wavs/yorubatts_00483.wav,David ni
|
| wavs/yorubatts_00484.wav,Mo ṣe é gẹ́gẹ́ bí àṣẹ rẹ
|
| wavs/yorubatts_00485.wav,Ẹ̀ kì í ṣe olórin
|
| wavs/yorubatts_00486.wav,Ẹ jọ̀ọ́ ẹ jẹun
|
| wavs/yorubatts_00487.wav,Ẹ̀yin kọ́ ni olórin
|
| wavs/yorubatts_00488.wav,Ó jó bí ẹni tí kì í rẹ́
|
| wavs/yorubatts_00489.wav,"Ta ò bá ti ṣiṣẹ́, a ò ba ní ra ile"
|
| wavs/yorubatts_00490.wav,Àwa n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00491.wav,Níbo ni Janet wà?
|
| wavs/yorubatts_00492.wav,Jẹ́ kí n ràn ẹ́ lọ́wọ́
|
| wavs/yorubatts_00493.wav,Ilé yin
|
| wavs/yorubatts_00494.wav,Jẹ́ kó jẹun
|
| wavs/yorubatts_00495.wav,Ìjọsìn yìí mú inú mi dùn
|
| wavs/yorubatts_00496.wav,Mi o rántí bóyá o jẹun
|
| wavs/yorubatts_00497.wav,gidigidi
|
| wavs/yorubatts_00498.wav,"Tí wọ́n bá ti mọ̀, wọ́n ò ní kọ́sẹ̀"
|
| wavs/yorubatts_00499.wav,Níbo ni wọ́n lọ?
|
| wavs/yorubatts_00500.wav,Wọ́n wá látí ṣèrànwọ́
|
| wavs/yorubatts_00501.wav,Nígbà ti
|
| wavs/yorubatts_00502.wav,Ilé yìí tóbi ju ti wọ́n
|
| wavs/yorubatts_00503.wav,Èló ni bàtà yìí?
|
| wavs/yorubatts_00504.wav,Orúkọ mi ni...
|
| wavs/yorubatts_00505.wav,Wọ́n ò jẹun
|
| wavs/yorubatts_00506.wav,Wọ́n n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00507.wav,Má jẹ́ kó sùn
|
| wavs/yorubatts_00508.wav,Bàtà rẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00509.wav,Ó fẹ́ràn rẹ púpọ̀
|
| wavs/yorubatts_00510.wav,láì
|
| wavs/yorubatts_00511.wav,"Nigba ti mo dé, mo rí i"
|
| wavs/yorubatts_00512.wav,Mo ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00513.wav,Ṣé o lè ràn mí lọ́wọ́?
|
| wavs/yorubatts_00514.wav,Ẹsẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00515.wav,Àwa kọ́ ni oníṣòwò
|
| wavs/yorubatts_00516.wav,"Tí ìwọ bá lọ sí London, o máa gbádùn"
|
| wavs/yorubatts_00517.wav,A kòkò jẹun ka tó lọ
|
| wavs/yorubatts_00518.wav,Wọ́n rìn-àjò láì sí James
|
| wavs/yorubatts_00519.wav,"Ti Janet ko bá ti ràn mí lọ́wọ́, m ba ti jìyà"
|
| wavs/yorubatts_00520.wav,tàbí
|
| wavs/yorubatts_00521.wav,Mo fẹ́ ko tẹ́tẹ́ sáré
|
| wavs/yorubatts_00522.wav,Mo máa lọ lónìí
|
| wavs/yorubatts_00523.wav,Bàtà wà lábẹ̀ ibùsùn
|
| wavs/yorubatts_00524.wav,pẹ̀lú
|
| wavs/yorubatts_00525.wav,Ẹsẹ̀ mi ń dun mi
|
| wavs/yorubatts_00526.wav,mẹjọ
|
| wavs/yorubatts_00527.wav,Kí ni ìdí tí a ra moto?
|
| wavs/yorubatts_00528.wav,David kọ́ ni olùkó
|
| wavs/yorubatts_00529.wav,A mọ̀ bí a ṣe ń jó
|
| wavs/yorubatts_00530.wav,Mo ní ìtẹ́lọ́rùn
|
| wavs/yorubatts_00531.wav,Mo sáré kíákíá
|
| wavs/yorubatts_00532.wav,Iru àpò wo ló ní?
|
| wavs/yorubatts_00533.wav,nigbagbogbo
|
| wavs/yorubatts_00534.wav,Wọ́n máa lọ ni ose to n bo
|
| wavs/yorubatts_00535.wav,Mo jẹ́ ọmọ ọdún méjìlá
|
| wavs/yorubatts_00536.wav,gẹ́gẹ́ bí
|
| wavs/yorubatts_00537.wav,eré
|
| wavs/yorubatts_00538.wav,"Ẹ jọ̀ọ́, jẹ́ kí n wọlé"
|
| wavs/yorubatts_00539.wav,Mo fẹ́ran ẹ
|
| wavs/yorubatts_00540.wav,tó fi jẹ́ pé
|
| wavs/yorubatts_00541.wav,Kò mọ̀ bí a ṣe ń kọrin
|
| wavs/yorubatts_00542.wav,Ó ò jẹ́ olùkó
|
| wavs/yorubatts_00543.wav,Ikọ
|
| wavs/yorubatts_00544.wav,Mo jẹun
|
| wavs/yorubatts_00545.wav,"To ba je emi, mi ò ní fọwọ́sowọpọ̀"
|
| wavs/yorubatts_00546.wav,Ẹ káalẹ́
|
| wavs/yorubatts_00547.wav,itura
|
| wavs/yorubatts_00548.wav,wọn
|
| wavs/yorubatts_00549.wav,Tẹ́lẹ̀
|
| wavs/yorubatts_00550.wav,Wọ́n ò lọ rárá
|
| wavs/yorubatts_00551.wav,David bẹ̀ mi pé kí n má bínú
|
| wavs/yorubatts_00552.wav,nigbagbogbo
|
| wavs/yorubatts_00553.wav,Iru ounjẹ wo la fẹ́ràn?
|
| wavs/yorubatts_00554.wav,Wọ́n máa lọ ni ojo meji to n bo
|
| wavs/yorubatts_00555.wav,Óun kọ̀ ló wá
|
| wavs/yorubatts_00556.wav,Ko tó lọ
|
| wavs/yorubatts_00557.wav,Ìrírí yìí mú kí n ronú
|
| wavs/yorubatts_00558.wav,Wọ́n ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00559.wav,Ẹ jọ̀ọ́
|
| wavs/yorubatts_00560.wav,Èwo ni wọ́n ra?
|
| wavs/yorubatts_00561.wav,Ó yẹ ka jẹun ní àkókò
|
| wavs/yorubatts_00562.wav,Ta ni?
|
| wavs/yorubatts_00563.wav,"Tó bá ti dé, a ò ba ni ronu"
|
| wavs/yorubatts_00564.wav,Mo fẹ́ kọ́ ẹ̀kọ́ látí di dókítà
|
| wavs/yorubatts_00565.wav,Ẹ̀yin ni
|
| wavs/yorubatts_00566.wav,Ko sí fonu níbí
|
| wavs/yorubatts_00567.wav,Kí ni ìdí tí o fe lọ?
|
| wavs/yorubatts_00568.wav,Ó ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00569.wav,Orí
|
| wavs/yorubatts_00570.wav,"Tó ò bá pè, a ò ní mọ̀"
|
| wavs/yorubatts_00571.wav,Iru orin wo ni wọ́n ń kọ?
|
| wavs/yorubatts_00572.wav,Mi ò ní pé dé
|
| wavs/yorubatts_00573.wav,Mo fẹ́ ọbẹ tàbí ìrẹsì
|
| wavs/yorubatts_00574.wav,Ó lọ ni ojo meji to koja
|
| wavs/yorubatts_00575.wav,Ó kì í ṣe olùkó
|
| wavs/yorubatts_00576.wav,Ó yẹ ka kòkò gbà á
|
| wavs/yorubatts_00577.wav,Àwọn n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00578.wav,Bàbá náà ní kí n ra ewé
|
| wavs/yorubatts_00579.wav,lọ
|
| wavs/yorubatts_00580.wav,"Tí wọ́n bá fẹ́, wọ́n ò ní kúrò"
|
| wavs/yorubatts_00581.wav,Mo wà dáadáa
|
| wavs/yorubatts_00582.wav,Ẹ̀ kì í kọrin
|
| wavs/yorubatts_00583.wav,Olùkọ́ ní kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kọ́wé
|
| wavs/yorubatts_00584.wav,"A rà oúnjẹ bí àmàlà, ìyán àti ẹ̀bà"
|
| wavs/yorubatts_00585.wav,Mo mọ̀
|
| wavs/yorubatts_00586.wav,"Tí m bá ti kówó pamo, m ba ti ra moto bayìí"
|
| wavs/yorubatts_00587.wav,Mi kì í ṣe olùkó
|
| wavs/yorubatts_00588.wav,Ó yẹ kí wọ́n lọ sùn
|
| wavs/yorubatts_00589.wav,bí
|
| wavs/yorubatts_00590.wav,Mo ní láti ra ilé
|
| wavs/yorubatts_00591.wav,Wọ́n ò ní ta a
|
| wavs/yorubatts_00592.wav,ìrora
|
| wavs/yorubatts_00593.wav,Ìwọ n jẹun
|
| wavs/yorubatts_00594.wav,Ìwọ
|
| wavs/yorubatts_00595.wav,òwò
|
| wavs/yorubatts_00596.wav,Má jẹ́ kí o sùn
|
| wavs/yorubatts_00597.wav,ẹja
|
| wavs/yorubatts_00598.wav,Ṣé o le bá mi ṣe?
|
| wavs/yorubatts_00599.wav,iṣu
|
| wavs/yorubatts_00600.wav,Ẹ̀ máa jẹun
|
| wavs/yorubatts_00601.wav,mo
|
| wavs/yorubatts_00602.wav,O ò jẹun
|
| wavs/yorubatts_00603.wav,Ìwọ lọ ṣáájú
|
| wavs/yorubatts_00604.wav,Orí fìfọ
|
| wavs/yorubatts_00605.wav,Mo ń jẹun làná
|
| wavs/yorubatts_00606.wav,Ko sí iwe lori tabili
|
| wavs/yorubatts_00607.wav,Mo kéré
|
| wavs/yorubatts_00608.wav,ìbànújẹ
|
| wavs/yorubatts_00609.wav,Mo bẹ̀ ọ pé ko má bínú
|
| wavs/yorubatts_00610.wav,Bóyá a máa rí David lọ́la
|
| wavs/yorubatts_00611.wav,Kò jẹun
|
| wavs/yorubatts_00612.wav,méjì
|
| wavs/yorubatts_00613.wav,"Lẹ́yìn náà, mo ń ṣiṣẹ́ ní ọ́fíìsì"
|
| wavs/yorubatts_00614.wav,Kò ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00615.wav,lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan
|
| wavs/yorubatts_00616.wav,O máa se òbẹ
|
| wavs/yorubatts_00617.wav,"To bá ti wá, a ò bá ní jáde"
|
| wavs/yorubatts_00618.wav,Nigbà wo ni ìdánwò náà?
|
| wavs/yorubatts_00619.wav,"Ó ṣiṣẹ́ takuntakun, tó fi jẹ́ pé wọ́n fún un ní ẹ̀bùn"
|
| wavs/yorubatts_00620.wav,tún
|
| wavs/yorubatts_00621.wav,"Jọ̀wọ́, kọ́ mi bí a ṣe"
|
| wavs/yorubatts_00622.wav,"Tó bá ṣiṣẹ́, kò ní jìyà"
|
| wavs/yorubatts_00623.wav,Ṣé o mọ̀ bí a ṣe ń kọrin?
|
| wavs/yorubatts_00624.wav,Bàtà wọn
|
| wavs/yorubatts_00625.wav,"Tí ẹ bá ti kọ́ ẹ̀kọ́, ẹ ò ní gbagbé"
|
| wavs/yorubatts_00626.wav,Jẹ́ kí n lọ
|
| wavs/yorubatts_00627.wav,Ẹ ò tóbi
|
| wavs/yorubatts_00628.wav,Wọ́n fẹ́ ka ṣiṣẹ́ pọ̀
|
| wavs/yorubatts_00629.wav,Ó dàbọ̀
|
| wavs/yorubatts_00630.wav,Wọ́n kì í ṣiṣẹ́ níbí
|
| wavs/yorubatts_00631.wav,òdo
|
| wavs/yorubatts_00632.wav,wọn
|
| wavs/yorubatts_00633.wav,Ẹ̀ ti lọ
|
| wavs/yorubatts_00634.wav,nítorí náà
|
| wavs/yorubatts_00635.wav,Mi ò ti sètán
|
| wavs/yorubatts_00636.wav,Kẹ tó dé
|
| wavs/yorubatts_00637.wav,Bàtà pupa
|
| wavs/yorubatts_00638.wav,Ẹ̀ ò ní jẹun
|
| wavs/yorubatts_00639.wav,ìlù
|
| wavs/yorubatts_00640.wav,dájú
|
| wavs/yorubatts_00641.wav,tẹ́tẹ́
|
| wavs/yorubatts_00642.wav,Nigbà wo ni wọ́n dé?
|
| wavs/yorubatts_00643.wav,Mo máa se òbẹ
|
| wavs/yorubatts_00644.wav,Ó bí mí pé ṣé mo mọ ọ
|
| wavs/yorubatts_00645.wav,ninu
|
| wavs/yorubatts_00646.wav,réré
|
| wavs/yorubatts_00647.wav,A ò ní jẹun
|
| wavs/yorubatts_00648.wav,Mo mọ̀ ọ gan-an
|
| wavs/yorubatts_00649.wav,Bá wa pa ina
|
| wavs/yorubatts_00650.wav,Mo wá láti London
|
| wavs/yorubatts_00651.wav,Ìwọ kọ́ ni akẹ́kọ̀ọ́
|
| wavs/yorubatts_00652.wav,Kò ní ta a
|
| wavs/yorubatts_00653.wav,Ṣé mo lè rí i?
|
| wavs/yorubatts_00654.wav,Kò sí níbí
|
| wavs/yorubatts_00655.wav,Awon lo jẹ́ ẹ
|
| wavs/yorubatts_00656.wav,rárá
|
| wavs/yorubatts_00657.wav,Àwọn
|
| wavs/yorubatts_00658.wav,Wọ́n kì í ṣe ọlọ́jọ́gbọ́n
|
| wavs/yorubatts_00659.wav,igi
|
| wavs/yorubatts_00660.wav,Ìwé wà lórí tábìlì
|
| wavs/yorubatts_00661.wav,Mo joko laarin won
|
| wavs/yorubatts_00662.wav,Wọ́n ò jẹ́ ọlọ́jọ́gbọ́n
|
| wavs/yorubatts_00663.wav,Mi ò ti jẹun
|
| wavs/yorubatts_00664.wav,Tẹ́tẹ́ lọ!
|
| wavs/yorubatts_00665.wav,Wọ́n rìn-àjò láì sí owó
|
| wavs/yorubatts_00666.wav,Mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́
|
| wavs/yorubatts_00667.wav,Ó ṣe iṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí mo ti sọ
|
| wavs/yorubatts_00668.wav,Aga wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ tábìlì
|
| wavs/yorubatts_00669.wav,wọn
|
|
|