raw_text
stringlengths
2
128k
r a b dikko r a b dikko je ara naijiria
wilberforce echezona wilberforce william chukudinka echezona je ara naijiria
àwọn ọmọ tiv àwọn ọmọ tiv je ara naijiria
kabeer gbaja-biamila kabeer gbàjàbíàmílà jẹ ara nàìjíríà ti orílẹ̀-èdè yorùbá agba bọ̃lù-ẹlẹ́sẹ̀ amẹ́ríkà
joseph gomwalk joseph gomwalk je ara naijiria
tariq hanna tariq hanna je ara naijiria
hao ge hao ge je ara naijiria
viktor ibekoyi viktor ibekoyi je ara naijiria
cecilia ibru cecilia ibru je ara naijiria
alvan ikoku alvan ikoku je ara naijiriati a bi ni ọjọ kínní oṣù kẹjọ ọdún 1900- ojo kejidinlogun oṣù kọkànlá ọdún 1972 o jẹ olukọniajijagbara ati olóṣèlú ìgbé ayé ti a bi ni ọjọ kínní oṣù kẹjọ 1900 ni amanagwu arochukwu ti a n pe ni ìpínlẹ̀ ábíá láti ọdún 1911 sí ọdún 1914ọ ka ìwé akẹkọ béèrè ni arochukwu government pr...
funmi iyanda olufunmilola aduke iyanda bíi ni ọjọ́ kẹtàdínlógbon oṣù keje ọdún 1971 tó gbajúmọ̀ lásán bí funmi iyanda jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ oníròyìn ní nàìjíríà ó ṣe atọkun ètò rẹ new dawn with funmi òun ni olùdarí of ignite media ní ọdún 2011 world economic forum pé ní olórí agbaye tí ó sì kéré forbes náà sì wí pé ó wà ...
jackson tugbeh jackson tugbeh je ara naijiria
joseph chike edozien joseph chike edozien je ara naijiria
t b joshua tèmítọ́pẹ́ balógun joshua tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1963 tí ó sì papò da ní ọjọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 2021 jẹ́ olùṣọ́ àgùtàn oníwàásù televangelist philanthropist òun ni olùdásílẹ̀ ilé-ìjọsìn the synagogue church of all nations scoan tí ó jẹ́ ilé-ìjọsìn tí ó tóbi tí ó sì tún ṣakóso em...
mak 'kusare mak 'kusare je ara naijiria
walter mbonu walter mbonu jẹ́ ará orílẹ̀-èdè nàìjíríà
muhammad ali pate muhammad ali pate je ara naijiria
oliver muoto oliver muoto jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tí ó ń gbé ní ìlú poland bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè poland oliver jẹ́ olókòwò ilẹ̀ poland
usim nduka usim nduka je ara naijiria
emmanuel nnadozie emmanuel nnadozie je ara naijiria
una nwajei una nwajei je ara naijiria
anthony nwakaeme anthony nwakaeme je ara naijiria
obi ilẹ̀ onitsha obi ilẹ̀ onitsha je ara naijiria
ojiako ezenne ojiako ezenne je ara naijiria
richard okonye richard okonye je ara naijiria
isidore okpewho isidore okpewho je ara naijiria awon iwe to ko the victims the last duty tides call me by my rightful name 2004 the epic in africa toward a poetics of the oral performance african oral literature backgrounds character and continuity once upon a kingdom myth hegemony and identity
nana olomu nana olomu je ara naijiria
olufunmilayo olopade olufunmilayo i olopade oontí a bí ní ọdún 1957 ní orílẹ̀-èdè naijiria jẹ́ oníṣègùn tó ní ṣe pẹ̀lú kíkọ́ nípa ẹ̀jẹ̀ súsú òun sì ni associate dean fún global health and walter l palmer distinguished service professor nínú ọ̀rọ̀ ìṣègún àti elétò ìlera ní yúnifásitì ti chicago ó tún ń ṣiṣẹ́ bíi olùdarí...
bandele omoniyi bandele omoniyi je ara naijiria
peter onumanyi peter onumanyi je ara naijiria
toyin raji toyin raji je ara naijiria
beko ransome-kuti beko ransome-kuti ti won bi 2 august 1940 10 february 2006 je dikita ninu ilu naijiria ti won fun ise ajafitafita ẹtọ eniyan
deola sagoe deola sagoe je ara naijiria
samsong samsong je ara naijiria
gbenga sesan gbenga sesan je ara naijiria
dele sosimi dele sosimi je ara naijiria
binta sukai binta sukai je ara naijiria
government tompolo government tompolo 1971- je ara naijiria ni oṣu kẹjọ ọdun 2022 muhammadu buhari tunse iwe adehun abojuto opo gigun ti agbegbe delta ti o ni ere pẹlu tempolo
f nnabuenyi ugonna f nnabuenyi ugonna je ara naijiria
hamza rafindadi zayyad hamza rafindadi zayyad je ara naijiria
salawa abeni sàláwà àbẹ̀ní álídù ni wọ́n bí ní 5 may 1961 ó jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀ èdè nàj̀íríà ó wá láti ìjẹ̀bú etí-òsà nị́ ìpínlẹ̀ ògùn ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin wákà kikọ nígbà tí ó ṣe orin tó sọọ́ di ìlú-mọ̀ọ́ka tí ó pè àkọ́lé rẹ̀ ní 'late general murtala ramat mohammed ní ọdún 1976 lábẹ́ ilé iṣẹ́ leader records orin yìí n...
bola abimbola bola abimbola je olorin ara naijiria
segun adewale ṣẹ́gun adéwálé jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọdún 1955 jẹ́ olórin tí ọ̀pọ̀ sì gbà wípé òun ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ orin yi-pọọ̀pù tí ó jẹ́ àdàlú orin funk jazz jùjú régè àti afró ìgbé ayé ré ọmọba ṣẹ́gun adéwálé ni wọ́n bí sí ilé ọóba tí òun náà sì jẹ́ ọrùn ìlẹ̀kẹ̀ pẹ̀lú nílùú ògbómọ̀ṣọ́ ní ìpí...
ambrose akinmusire ambrose akinmusire je olorin ara naijiria
batile alake batile alake je olorin ara naijiria omo bibi ilu ijebi-igbo ni ipinle ogun
tony allen musician tony allen musician je olorin ara naijiria
alamu atatalo àlàmú tátalọ̀ ni olùdásílẹ̀ orin ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ orin tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ orin ìbílẹ̀ yorùbá àlàmú jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn ó sì gbajúmọ̀ gidi ní gbogbo ilẹ̀ yorùbá látàrí ìwọ́hùn àti ìṣọwọ́ lè orin sákárà rẹ̀ ní àsìkò ọdún 1950 sí ọdún 1960 amọ́ iyì rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ń wọmi nígbà tí àwọn alátakò rẹ̀...
ayinde bakare ayinde bakare je olorin ara naijiria
adé bantu adé bantu je olorin ara naijiria
jonathan cyril jonathan cyril je olorin ara naijiria
noel dacosta noel dacosta je olorin ara naijiria
i k dairo isaiah kehinde dairo mbe 19301996 je olorin ara naijiria itokasi saiah kehinde dairo mbe 1930 - 7 kínní 1996 jẹ́ gbajúgbajà olórin jùjú ọmọ nàìjíríà igbesi aye ibẹrẹ ik a bi dairo ni ilu offa ti o wa ni ode oni ipinle kwara idile rẹ jẹ akọkọ lati ijebu-jesa ṣaaju ṣiṣi lọ si offa o lọ si ile -iwe alakọbẹrẹ kri...
darey darey je olorin ara naijiria
dr sid dr sid sidney onoriode esiri jẹ́ olórin ọmọ orílè-èdè naijiria a bíi ní ọjọ́ kínní oṣù karùn-ún ọdún 1980 ní ikeja ìpínlè èkó orílẹ̀-èdè naijiria ó jẹ́ ẹni tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí dr sid ó sì tún jẹ́ ẹni tí ó ń kọ orin sílẹ̀ tí ó tún jẹ́ akọrin ìgbà èwe rẹ̀ dr sid wá látì ìpìńlẹ̀ deltá ṣùgbọ̀ń ìpìńlẹ́ èkò ńì wọ̀ń ...
dr alban dr alban je olorin ara naijiria
lazarus ekwueme lazarus ekwueme je olorin ara naijiria
eldee eldee je olorin ara naijiria
dizzy k falola dizzy k falola je olorin ara naijiria
majek fashek majekodunmi fasheke tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí majek fashek jẹ́ olùkọ orin atajìtá àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di ìlú-mọ̀ọ́ká olòlórin ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní àsìkò ọdún 1988 fún àwo orin rẹ̀ tí ó gbé jáde lásìkò yí tí ó pè ní _onígbèkùn ọkàn prisoner of conscience àti àwọn orín rẹ̀ ọlọ́kan ò jọ̀ka...
gt da guitarman gt da guitarman je olorin ara naijiria
ice prince panshak henry zamani tí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ ń jẹ́ ice prince ni a bí ní ọgbọ́n ọjọ́ oṣù kẹwàá ọdún 1984 ó jẹ́ akọrin hip hop ọmọ nàìjíríà tí ó ń kọ orin sílẹ̀ tí ó tún ṣeré orí ìtàgé òkìkí rẹ kàn nígbàtí ó gbé oleku síta orin náà jẹ́ ọ̀kan lára orin tí wọn ṣe àdàlú rẹ jùlọ ni orílè èdè nàìjíríà ó gba ipò kín...
2face idibia innocent ujah idibia tí a bí sí ìlú jos ìpínlẹ̀ plateau state orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ 2baba jẹ́ olórin orílẹ̀ èdè nàìjíríà akọrin sílẹ̀ agbọ́rin jáde àti onísẹ́ àdáni ní oṣù keje odun 2014 ó yan 2face idibia gẹ́gẹ́ bí orúkọ ìtàgé rẹ̀ ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin ilẹ̀ áfíríkà tó ń kọ ...
ego ihenacho ego ihenacho ogbaro je olorin ara naijiria o korin leyin bisade ologunde lagbaja fun odun mewa omo bibi ipinle imo ni lo si ile iwe alakobere sentira ati ile iwe giga prestigiuos ikeja ni ilu ekooo gbe igba orin re ni 2007 ti egbe re n je indigoo para po sise pelu sunny nneji tosin martins ayanbirin asa at...
sólómọ́n ilori sólómọ́n ilori je olorin ara naijiria
waje waje tí orúko àbíso rè njé aituaje iruobe jé olórin ará naijiria ó kókó gba ìdánimò léyìn ìgbà tí ó kópa nínú àtúnse orin omoge mi típ-square ko wáje tún kópa nínú orin won tí ó gbajú gbajà tí ó nje do me láfikún ó fi ohùn rè kún orin thief my kele tí banky w one naira tí ó je ti mi ni odun 2016 waje je okan lara ...
jesse jagz jesse jagz je olorin ara naijiria
tunde jegede tunde jegede' je olorin ara naijiria
peter king peter king adéyoyin osubu tí a mọ̀ sí peter king jẹ́ gbajú-gbajà olorin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ nàìjíríà tí ó mọ̀ nípa ìlò onírúurú irinṣẹ́ èlò orin lọ́pọ̀ ìgbà ó fẹ́ràn láti máa fọn fèrè tí a mọ̀ sí saxphone tí ó sì ma fi ń gbé orin jáde àti ìlù jáàsì fún ìgbádùn àwọn tó ní ìfẹ́ sí irúfẹ́ orin rẹ̀ peter king g...
kokoro olórin benjamin ‘kokoro’ aderounmu 25 february 1925 25 january 2009 je olorin ara naijiria won bi sinu idile ọba ni owo nipinlẹ ondo o si di afọju nigbati o jẹ ọmọ ọdun mẹwa o ṣe agbekalẹ aṣa alailẹgbẹ ti orin pẹlu ilu ati tanbourin ni odun 1947 o lo si ilu eko nibi to ti pade awon olorin ilu bii ayinde bakare b...
kola ogunkoya kola ogunkoya je olorin ara naijiria
seun kuti oluseun anikulapo kuti ti a bi ni ojo kokanla osu kini odun 1983 ti opolopo mo si seun kuti je gbajugbaja olorin omo orile-ede naijiria seun ni o n darii egbe olorin baba re egypt 80
lagbaja lagbaja tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ bísádé ológundé tí a bí ní ìlú èkó ni ọdún 1960 jẹ́ gbajúgbajà akọrin afrobeat ọmọ orílè èdè nàìjíríà gbogbo ènìyàn mọ akọrin yí sí lágbájá nítorí wípé ó jé ẹni tí ó fẹ́ràn láti máa lo ìbòjú láti dáàbò bo ara rẹ kí wọn má le dáa mọ̀ ó gbàgbọ́ nínú àtúntó ìlú láti ipasẹ̀ orin k...
mi mi je olorin ara naijiria
kevin mcdaid kevin mcdaid tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1984 jẹ́ akọrin ará ìlú gẹ̀ẹ́sì orílè-èdè nàìjíríà ni wọ́n bí kevin sí tí wọ́n sì tọọ dàgbà ni ìlú england ni newcastle upon tyne wọ́n mú dáradára gégé bíi ọmọ ẹgbẹ́ ti british boy band v èyí tí ó darapọ̀ mọ́ ní ọdún 2003 pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin mérin mìíràn ẹgb...
dan maraya dan maraya je olorin ara naijiria
prince nico mbarga prince nico mbarga je olorin ara naijiria
weird mc weird mc je olorin ara naijiria
tunde nightingale earnest olátúndé thomas túndé nightingale je olorin ara naijiria gbajúmọ̀ olórin ọmọ orílẹ́-èdè nàìjíríà earnest olátúndé thomas tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí túndé nightingale tàbí the western nightingale jẹ́ oní gìtá àrà tó ń kọ ẹ̀yà orin jùjú ní èyí tó ṣe àwòkọ́ṣe irúfẹ́ orin ìbílẹ̀ ti ọ̀gbẹ́ni túndé king...
nneka nneka lucia egbunna a bii ni ọjọ́ kẹrìnlelogun ọdún 1980 o jẹ olorin àdàlú ilẹ nàìjíríà àti jamaní hip/soul á máa ṣe àkọọlè irúfẹ́ orin yìí àti kíkọ orin náà ìgbé- ayé ẹ nneka tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ anambra tíí ṣe ẹ̀yà ìgbò tí ìyá a rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè jamani a bí nneka bẹ́ẹ̀ la tọ dàgbà nílùú war...
nnena nnena je olorin ara naijiria
abass akande obesere abass àkàndé òbésèré tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ọmọ rápálá ojoibi 28 january ọdún 1965 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin fújì ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìràwọ̀ òbésèré tán nípa orin alùfàǹṣá fújì tí ó máa ń kọ orin àṣàkáṣà ní ó pọ̀jù nínú àwọn orin fújì rẹ̀ kódà ó pe ara rẹ̀ ní...
ebenezer obey ebenezer obey jẹ́ gbajúgbajà olórin jùjú láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kẹ́ta oṣù kẹrin ọdún 1942 àpèjá orúkọ rẹ̀ ni ebenezer rẹ̀mílẹ́kún àrẹ̀mú ọláṣùpọ̀ obey-fabiyi ìlú idogo ní ẹnu ibodè tí ó pa ààlà orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ni a ti bi ebenezer obey orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ni chief commander
jide obi jide obi je olorin ara naijiria
obiwon obiwon je olorin ara naijiria
ogbogu okonji ogbogu okonji je olorin ara naijiria
funsho ogundipe funsho ogundipe je olorin ara naijiria
sonny okosun sonny okosun je olorin ara naijiria
babá ken okulolo babá ken okulolo je olorin ara naijiria
victor olaiya victor abímbọ́lá ọláìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí dr victor ọláìyá ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1930 ó sìn jáde láyé lọ́jọ́ kejìlá oṣù kejì ọdún 2020 31st december 1930 - 12th february 2020 jẹ́ gbajúmọ̀ afọnfèrè-kọrin afẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun bàbá gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àg...
babátúndé ọlátúnjí
yusuf olatunji yusuf olatunji 1905-1978 tó gbajúmọ̀ bíi baba l’ẹ́gbàá jẹ́ olórin àti onílù sákàrà ara naijiria yusuf ọlátúnjí tí a tún mọ̀ sí bàbá lẹ́gbá 1905 -1978 ni ó jẹ́ olórin orin sákárà tí ó sì gbé orin sákárà ga ní ilẹ̀ yorùbá wọ́n bí yusuf ní ọdún 1905 tàbí 1906 ni abúlé kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ gbegbinlawo ní ì...
joseph omotoye joseph omotoye je olorin ara naijiria
onyeka onwenu onyeka onwenu ọjọ́ìbí ọjọ́ mọ́kànlélógbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1952 jẹ́ oniroyin olórin òṣèré a jíjà gbàrà ati òṣèlú ni nàìjíríà ó wá láàrin àwọn tí ó má ń dá jọ fún ètò x factor tẹ́lẹ̀ òun ni alága tẹ́lẹ̀ fún àṣà àti ìṣe fún ìpínlè imo òun ni adarí àti olórí aláṣẹ fún ìdàgbàsókè àwọn obìnrin ní orílè èdè ìbẹ̀...
william onyeabor william onyeabor je olorin ara naijiria
saheed osupa saheed osupa je olorin ara naijiria
sir shina peters sir shina peters je olorin ara naijiria
plantashun boyz plantashun boyz je olorin ara naijiria
prince adekunle prince adekunle je olorin ara naijiria
p-square p-square je olorin ara naijiria
muhamman shata muhamman shata je olorin ara naijiria