raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
jim patterson james patterson c 1928 16 december 2012 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ti orílẹ̀-èdè scotland patterson jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó máa ń gbá bọ́ọ̀lù tó pọ̀ jù lọ sáwọn fún ẹgbẹ́ dumfries queen of the south pẹ̀lú góòlù 251 |
michael nozik michael nozik jẹ́ ará ìlú america tó máa ń gbé fíìmù jáde ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti bafta fún fíìmù the motorcycle diaries lábẹ́ ìsòrí àwọn fíìmù tí kì í ṣe ti èdè gẹ̀ẹ́sìní ọdún 2004 lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni love in the time of cholera syriana quiz show àti the legend of bagger vance àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀ òun ló ṣag... |
akojọ awọn agbabọọlu ni ilu scotland nipasẹ nọmba awọn ibi-afẹde ajumọṣe atẹle ni atokọ ti awọn agbabọọlu ti o ti gba o kere ju igba awọn ibi-afẹde liigi ile ni bọọlu liigi scotland eyi pẹlu awọn ifarahan ati awọn ibi-afẹde ti awọn oṣere iṣaaju ninu awọn idije liigi ti ile ti o tẹle nikan nitori awọn asopọ isunmọ laari... |
queen's counsel bį' ótiwà nį'àkosílè🧭🖇 |
david wilson agbábọ́ọ̀lù david wilson tí wọ́n bí ní 17 december 1908 tó sì ṣaláìsï ní 22 february 1992 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì tó gbá bọ́ọ̀lù fún hamilton academical fc àti stranraer fc gẹ́gẹ́ bí i ọkàn lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà iṣẹ́ tó yàn láàyò ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù tó máa ń góòlù jù ó gbá ... |
dumfries dumfries jẹ́ ọjà àárín ìlú ó sì fìgbà kan jẹ́ ọjà fún àwọn ọlọ́lá àti lọ́balọ́ba ní dumfries àti galloway ní scotland lẹ́bàá etí odò nith saájú kó tó di ọba scots robert the bruce pa orogún rẹ̀ ìyẹn red comyn ní greyfriars kirk ní ìlú ní ọdún 1306 young pretender ní ilé-iṣẹ́ rè ní agbègbè náà títí wọ òpin ọdún... |
international hockey federation international sports governing body organizing field hockeyojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the governing body of field hockey fún the governing body of ice hockey ẹ wo international ice hockey federation international hockey federation tí a gé kúrú tí gbogbo èèyàn sì mọ̀ sí fih ó jẹ́ àjọ tó ṣe àm... |
china girl china girl jẹ́ fíìmù ọdún 1987 kan tó kún fún ìwúnilórí àti àhésọ èyí tí abel ferrara jẹ́ olùdarí fún tí nicholas st john tó jẹ́ alábàáṣiṣẹ́pọ̀ rẹ̀ kọ sílẹ̀ ìtàn china girl jẹ́ fíìmù kan tó fẹ́ jọ ti romeo and juliet ìlú manhattan ni ìbùdó-ìtàn ìtàn náà sì dá lé ọ̀dọ́mọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ tony láti... |
ọgbẹlẹ ni òrilẹ ede naìjìrìá ọgbẹlẹ fun igba pipẹ ni órilẹ ede naijiria ti jasi iparẹ̀ awọn igi koriko ati ilẹ ti a fin sin maalu tabi gbin kan ókó lati ri ilẹ fun oko ati nkan isin awọn oloko ati dàran dàran ni wọn maa ngbiyanju lati lọsi agbegbe tuntun eyi lo maa ṣaba jasi jakidijagan awọn oloko ati dàran dàran maa n... |
bob mcphail robert lowe mcphail ojo karun-le-logun oṣu kẹwa ọdun 1905 si ojo kerin-le-logun oṣu kẹjọ 2000 jẹ agbabọọlu alamọdaju ara ilu scotland kan ti o ṣere fun airdrieonians rangers ati aṣoju scotland iṣẹ-ṣiṣe airdrienians ti a bi ni barrhead mcphail bẹrẹ iṣẹ rẹ ni ẹgbẹ glasgow junior pollok o forukọsilẹ fun airdri... |
c j obasi cj obasi tí wọ́n tún máa ń pè ní fiery tàbí the fiery one jẹ́ olùdarí fíìmù ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà òǹkọ̀wé fíìmù àti alátùnńtò sórí fíìmù òun ló darí fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ojuju tí wọ́n ṣàfihàn ní africa international film festival ní november 2014 ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ fún fíìmù tó dára jù lọ ní nàìjíríà ó... |
hughie ferguson hugh ferguson ojo keji oṣu kẹta 1895 - ojo kejo oṣu kini ọdun 1930 jẹ agbabọọlu alamọdaju ara ilu scotland kan ti a bi ni motherwell o ṣere fun parkhead ni ipele kekere bi magbowo ati pe o jẹ ọkan ninu awọn oṣere ọdọ ti o wa julọ julọ ni ilu scotland ṣaaju ki o to forukọsilẹ fun ẹgbẹ ilu rẹ lati bẹrẹ iṣ... |
toka mcbaror toka mcbaror jẹ́ aṣagbátẹrù fíìmù tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì tún jẹ́ olùdarí fíìmù and music video director tí wọ́n bí tí ó dàgbà tí ó sì ń gbé ní ìpínlẹ̀ kaduna ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àmọ́ tí ó wà láti ìpínlẹ̀ delta ó gbà àmì-ẹ̀yẹ fún kada river ní ọdún 2018 toronto international nollywood film f... |
janet yang janet yang tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1956 jẹ́ olùṣe fíìmù àti ààrẹ academy of motion picture arts and sciences lọ́wọ́ lọ́wọ́ janet jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà yang àwọn eré janet tí ó ti fi gba àmì ẹyẹ ni the joy luck club the people vs larry flynt dark matter zero effect shanghai calling high cri... |
slavery in tunisia ìkonilérú ní tunisia jẹ́ ìfihàn kan pàtó ti ìṣòwò ẹrú arab èyí tí a parẹ́ ní ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1846 nípasẹ̀ ahmed i bey tunisia wà ní ipò tí ó jọra sí ti algeria pẹ̀lú ipò agbègbè tí ó so pọ̀ mọ́ àwọn ọ̀nà trans-saharan gan gan ó gba àwọn ọkọ̀ ayọ̀kẹlẹ láti fezzan àti ghadamès èyí... |
nnimmo bassey nigerian activist nnimmo bassey a bini ọjọ kọkanla óṣu june ọdun 1958 jẹ ayaworan ilẹ ti naijiria ajijagbara fun àyika onkọwe ati akewi to ṣè agbatẹ̀ru ọrẹ ti ayika agabaye lati ọdun 2008 de 2012 igbèsi àyè ati ẹkọ nnimmo bassey bassey kẹkọ nipa ayaworan ilè to si ṣiṣẹ ijọba fun ọdun mẹwa lẹyin naa lo tẹs... |
liberland liberland ni ifowosi ti a pe ni ominira ominira ti liberland jẹ micronation ti o bẹrẹ lori ilẹ ti ko ni ẹtọ ni apa iwọ-oorun ti odò danube laarin croatia ati serbia liberland jẹ idasile ni ọjọ 13 oṣu kẹrin ọjọ 2015 nipasẹ alakitiyan ominira czech vít jedlička oju opo wẹẹbu liberland osise sọ pe orilẹ-ede naa ... |
jagun jagun fíìmù nàìjíŕà jagun jagun jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí netflix gbé jáde ní ọdún 2023 ó jẹ́ fíìmù àgbéléwò ajẹmọ́-ìtàn-akọni èyí tí fẹ́mi adébáyọ̀ àti euphoria360 media ṣàgbéjáde adebayo tijani àti tope adebayo salami ni olùdarí eré náà lára àwọn akópa eré náà ni femi adebayo lateef adédiméjì bimbo ademoye faithia ... |
ádèsuwà ọbàsùyi nigeria climate change activist ádèsuwà ọbàsùyi a bini òṣu february ọdun 1990 jẹ ónimọ nipa ayika ti ilẹ naijiria ajijagbara lori ayipada afẹfẹ tabi óju ọjọ oludasilẹ ti sustainable africa cities and communities initiative eyi jẹ awujọ aladani to da lori ẹgbin ati isakoso ẹgbin data ni ilẹ naijiria ati ... |
willie reid bọọlu afẹsẹgba ti a bi ni ọdun 1884 william reid 3 may 1884 - 13 may 1964 jẹ agbabọọlu agbabọọlu agbaye ti ilu scotland ati oluṣakoso ti o ṣere bi ikọlu ti ndun ọmọ ologba bibi ni baillieston lanarkshire reid bẹrẹ iṣẹ agba rẹ ni ọdun 1903 pẹlu morton ẹniti o darapọ mọ baillieston thistle o gba awọn ibi-afẹd... |
desmond màjẹkòdùnmì nigerian climate activist desmond òlùmùyiwá màjẹkòdùnmì a bini óṣu june ọdun 1950 jẹ ònimọ nipa ayika ti ilẹ naijiria desmond jẹ alaga ti ipinlẹ lekki ti igbo ilu ipinlẹṣẹ ibugbe awọn ẹranko ati olugbalejo ti redio ti green hour lori iroyin naijiria 993 fm màjẹkòdùnmì jẹ̀ ounkọwe olorin àgbẹ ati óṣè... |
tom draper ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ tom dreaper thomas edward draper tí ọjọ́ ìbí é jó oh kẹẹ̀dọgun osù kọkànlá ọdún 1996 jẹ́ ọ̀kan lára eléré agbá ice hockey tí ipò é níbẹ̀ sì jẹ́ asọ́ ibi awon goaltender wọ́n yán àn ní igbà 165th lápapọ̀ ní ipò kẹjọ ní ẹ̀kẹ̀jọ ní winnipeg jets ní ọdún 1972-96 ní nhl entry draft èyí tí ... |
kris draper canadian ice hockey player kristopher bruce kris draper tí wọ́n ní oṣù kàrún-un ọdún 1971 sí canada jẹ́ ọ̀kan lára eléré agbá hockey tí ó sì jẹ́ olùdarí àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́ fún àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀dé àti olùrànlọ́wọ́ gbogbogbò fún detroit red wings tí ẹgbẹ́ rẹ̀ sí gbà hockey fún sáà mẹ́tàdínlógún ní gbogbo ìgba tó fí ... |
salah zulfikar egyptian actor and producer salah el-din ahmed mourad zulfikar lárúbáwá tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kìíní ọdún 1926 tí ó sì fi ayé silẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejìlá ọdún 1993 jẹ́ òṣeré àti olùṣe fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè íjíbítì nígbà ayé rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè íjíbítì kí... |
hunturu igba otutu igba otutu jẹ akoko otutu ati kurukuru pupọ ati ni awọn orilẹ-ede kan ọpọlọpọ omi yinyin wa nigbati igba otutu ba de igba otutu ni afirika ni ilẹ afirika igba otutu wa lati kẹrin si oṣu kẹjọ ni ọdun kọọkan igba otutu ni europe ni awọn orilẹ-ede yuroopu igba otutu jẹ eyiti o wọpọ julọ lati oṣu kini si... |
ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà constitutional human rights ìwé-òfin ọdún 1999 ni ó ń dáàbòbò ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà human rights in nigeria nígbà tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ṣe àwọn àtúnṣe gbòógì nínú ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ní abẹ́ ìwé-òfin yìí àjọ àbọ̀ àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ ẹnìyàn ní orílẹ̀-èdè america ti ọ... |
erosion surface ogbara dada ninu ẹkọ nipa ẹkọ nipa ẹkọ nipa ilẹ-aye ati geomorphology ilẹ ogbara jẹ dada ti apata tabi regolith ti a ṣẹda nipasẹ ogbara kii ṣe nipasẹ ikole fun apẹẹrẹ awọn ṣiṣan lava ifisilẹ erofo tabi iṣipopada aṣiṣe erosional roboto laarin awọn stratigraphic gba ti wa ni mo bi unconformities sugbon ko... |
afefe orile-ede naijiria ojú-ọjọ́ nàìjíríà jẹ́ ilẹ̀ olóoru jù lọ naijiria ni awọn agbegbe oju-ọjọ mẹta ọtọtọ awọn akoko meji ati aropin iwọn otutu laarin 21 °c ati 35 °c awọn eroja pataki meji ṣe ipinnu iwọn otutu ni nigeria giga ti oorun ati ijuwe oju-aye gẹgẹbi a ṣe pinnu nipasẹ ibaraẹnisọrọ meji ti ojo ati ọriniinit... |
adolph zukor hungarian-american film producer 18731976 adolph zukor ọjọ́ keje oṣù kíni ọdún 1873 ọjọ́ kẹ̀wá oṣù kẹfà ọdún 1976 jẹ́ òṣeré ọmọ orílẹ̀ èdè hungary mọ́ amẹ́ríkà tí ó gbajúmò gẹ́gẹ́ bi ọkàn lára àwọn mẹ́ta tí ó dá paramount pictures kalẹ̀ ó ṣe àgbéjáde the prisoner of zenda ní ọdún 1913 ìpìlẹ̀ a bí zukor sín... |
bakolori dam dam bakolori wa ni ipinle sokoto ni ariwa iwọ-oorun naijiria o ti pari ni ọdun 1978 ati ifiomipamo rẹ ti o kun nipasẹ ọdun 1981 o jẹ agbami nla ti o wa ni odo sokoto ti o wa ni odo rima eyiti o jẹ ki o jẹ odo niger omi lati inu idido naa pese iṣẹ irrigation bakolori idido naa ni agbara ti awọn mita onigun ... |
ishaya bako ishaya bako tí a bí ní ọjọ́ ọjọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1986 jẹ́ olùdarí fíímù nàìj́iríà àti òǹkọ̀wé fíimù ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí-ayé ẹ̀ ìlú kaduna ni wọ́n bí i níbi tó ti gbé ní gbogbo ayé rẹ̀ tó sì tún padà lọ sí ìlú lọ́ńdọ̀nù níbi tó ti kàwé ní ilé-ẹ̀kọ́ fíìmù lọ́ńdọ̀nù iṣẹ́-ṣíṣe lẹ́yìn tí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ fíímù ... |
saint obi obinna nwafor 9 tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1965 tí ó sì kú ní ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 2023 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí saint obi jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà olóòtú fíímù àti olùdarí fíìmù òbí ni a mọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínú fíímù candle light state of emergency sakobi goodbye tomorrow heart of g... |
odo sokoto odo sokoto eyiti a mo si gulbi 'n kebbi tele je odo kan ni ariwa-iwoorun naijiria ati odo odo niger orisun odo naa wa nitosi funtua ni guusu ti ipinle katsina bii ni ila taara lati sokoto o nṣàn ariwa-iwọ-oorun ti o kọja af gusau ni ipinle zamfara nibiti omi-omi gusau ṣe agbekalẹ omi ti o pese omi fun ilu na... |
priscilla achapka nigerian environmental activist priscilla achapka jẹ ajijagbara onimọ ayika ti ilẹ naijiria priscilla jẹ oludasilẹ ati ààrẹ agbaye ti awujọ awọn obinrin ti wọn mujoto ayika eyi ti ólóyinbo pe ni women environment programme wep ajọ yi jẹ eyi ti o maa npèsè alagbero ojutu fun iṣóró óójójumọ ninu eto ayi... |
chief daddy fíìmù nàìjíríà chief daddy jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè nàìjíríàtó jáde ní ọdún 2018 tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ niyi akinmolayan tí bode asianbi sì ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ tí mosunmola abudu àti temidayo abudu sì ṣàgbéjáde ní oṣù kejìlá ọdún 2018 ọ̀pọ̀ àwọn ògbóǹtarìgì òṣèré bí i funke akindele bello kate hens... |
jagun jagun |
king of thieves 2022 film king of thieves agẹṣinkólé jẹ́ ọ̀kan lára àọn fíìmù orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2022 èyí tí femi adebayo ṣàgbéjáde tí tope adebayo àti adébáyọ̀ tìjání sì darí ọ̀pọ̀ àwọn ògbóǹtarìgì òṣèré bí i odunlade adekola femi adebayo toyin abraham broda shaggi adebowale debo adedayo aka mr macar... |
segun arinze segun arinze tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ segun padonou aina tí wọ́n bí ní ọdún 1965 jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríà àti òǹkọrin ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ òun ni àkọ́bí láàárín àwọn ọmọ méje tí lydia padonu bí ìlúbadagry ní ìpínlẹ̀ èkó ló ti wá ilé-ìwé victory college of commerce ní ilorin ló... |
antar laniyan antar laniyan jẹ́ ògbóǹtarìgì òṣèrékúnrin aṣàgbéjáde eré àti olùdarí eré ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ̀ ìlú òṣogbo tó jẹ́ olú-ìlú ọ̀ṣun ní apá ìwọ-oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ni wọ́n bí laniyan sí ìlé-ìwé baptist secondary school ni ó ti gba ìwé-ẹ̀rí waec ní ìpínlẹ̀ èkó kó tó di pé ó wá lọ sí yunifásítì ìl... |
tádé ògìdán |
chico ejiro |
victor osuagwu victor osuagwu jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó ti gba àmì-ẹ̀yẹ ní city people entertainment awards ó sì fìgbà kan jẹ́ ààrẹ̀ ti actors guild of nigeria ẹka ti ìpínlẹ̀ èkó ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mbaise ní ipinle imo ni osuagwu ti wá ìlú surulere ní ìpínlẹ̀ èkóló dàgbà s... |
battle on buka street battle on buka street jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí funke akindele àti tobi makinde darí funke ayotunde akindele faan àti filmone studios ló pawọ́ pọ̀ ṣagbátẹrù fíìmù yìí wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù yìí ní ọjọ́ 16 oṣù kejìlá ọdún 2022 tó sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àríwísí fíìmù náà di àseyọr... |
nkem owoh nkem owoh tí wọ́n bí ní ọjọ́ 7 oṣù february ọdún 1958 jẹ́ òṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2008 ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti african movie academy lábẹ́ ìsọ̀rí òṣèrékùnrin tó jẹ́ olú ẹ̀dá-ìtàn tó dára jù lọ fún àwọn ìkópa rè nínú fíìmù orílẹ̀-èdè nàìjíríà bí i stronger than pain ìgbésí ayé rẹ̀ ... |
aniebiet inyang ntui nigerian diplomat ọjọgbọn aniebiet inyang ntui jẹ afọrọwèrọ ati ònimọ ayika to ti ṣoju fun eu ti óju ọjọ europe pact lati ọdun 2022 óṣu december arabinrin naa ṣè alakoso awọn panel ni òniruru apejọ ti united nations ni ọdun 2022 to waye ni montreal canada summit ti bali g20 ọdun 2022 ni ilu indones... |
ọmọ onílé ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the type of reptile fún ìtumọ́ míràn ẹ wo ọmọ onílé ìṣojútùú ọmọ onílé tàbí ọmọnlé tàbí ọmọọ́lé jẹ́ ẹranko kékeré tí ó ma ń jẹ àwọn kòkòrò àti labalábá ìrísí rẹ̀ dàbí ti alángbá kò sí ibi tí ọmọnlé kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé àyà fi ibi tí wọ́n ń pe ní antarctica tí ó tutù jùlọ lórilẹ̀ àgbáy... |
jimmy jones bọọlu afẹsẹgba ti a bi ni ọdun 1928 james jones ojo marundinlogbon osu keje odun 1928 - ojo ketala osu keji odun 2014 jẹ ọmọ ẹgbẹ́ ọmọ ireland ti àríwá o jẹ oludari awọn góòlù ninu itan ere bọọlu irish league pẹlu apapọ awọn góòlú ẹgbẹta o le meje gẹgẹbi rsssf o ti gba awọn idije diẹ sii ju ẹgbẹrin ati mẹsa... |
josef bican josef pepi bican 25 oṣu kẹsan ọdun 1913 12 oṣu kejila ọdun 2001 jẹ ẹlẹsẹ bọọlu ara ilu austrian-czech kan ti o ṣe bọọlu afẹsẹgba o ni imọran nipasẹ rsssf bi ẹni-afẹde keji-julọ pataki julọ ninu itan-akọọlẹ lẹhin erwin helmchen pẹlu awọn ibi-afẹde 950 ti o gba wọle ni awọn ere-idije osise 624 2 o ṣe aṣeyọri ... |
fernando peyroteo fernando baptista de seixas peyroteo de vasconcelos 10 oṣu kẹwa 1918 28 oṣu kọkanla ọdun 1978 jẹ ẹlẹsẹ ẹlẹsẹ ara ilu pọtugal kan ti o ṣe bọọlu afẹsẹgba o lo gbogbo iṣẹ amọdaju rẹ pẹlu sporting cp ti o ṣe afẹri awọn ibi-afẹde 544 ni gbogbo awọn idije ti o ṣẹgun awọn akọle pataki 11 ati pe o jẹ ade ti i... |
jan janszoon janszoon van haarlem ti a mọ si reis mourad the younger c 1570 c 1641 jẹ apaniyan dutch ti tẹlẹ ti o di corsair barbary ni ottoman algeria ati republic of salé lẹhin ti o ti gba nipasẹ awọn ẹlẹṣin algerian kuro ni lanzarote ni ọdun 1618 o yipada si islam o si yi orukọ rẹ pada si mourad o di ọkan ninu oloki... |
kashim ibrahim library ile-ikawe kashim ibrahim jẹ ọkan ninu ile-ikawe ile-ẹkọ giga ti afirika ti o wa ni ogba akọkọ ti ile-ẹkọ giga ahmadu bello ni zaria nigeria o ti wa ni commonly tọka si bi kil nipasẹ awọn abusites ile-ikawe naa jẹ ọkan ninu awọn ile-ikawe ile-iwe giga julọ ni nigeria ni awọn ofin ti awọn ohun elo ... |
kelvin ikeduba kelvin ngozi ikeduba ti a bi ni 21 oṣu kẹjọ ọdun 1976 jẹ oṣere ọmọ orilẹ-ede naijiria kan ti o ni ọdun 2014 gba ẹbun naa fun oṣere ti o dara julọ lori oṣere ni awọn awards ile-ẹkọ fiimu yoruba movie ymaa ati pe o jẹ laipẹ ti a mọ fun oniruuru rẹ ninu ile-iṣẹ fiimu fiimu naijiria bi o ti ṣe ifihan ninu aw... |
odo katsina ala katsina ala tabi katsina-ala jẹ odo kan ni agbedemeji naijiria ti o wa laarin aarin igbanu rẹ ó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí odò ńlá kan ní odò benue ní nàìjíríà orisun odo naa wa ni awọn agbegbe giga bamenda ni ariwa iwọ-oorun cameroon ó ń ṣàn ariwa-iwọ-oorun ni ilu kamẹra ti n kọja aala naijiria cameroon si naij... |
ìfómipamọ ti lagdo ifómipamọ ti lagdo jẹ ìfómipamọ to wa ni apa ariwa ti ilẹ cameroon ni ódó benue ni basin ti niger àdàgun naa bo area ti 586 km2 ìtan ìfomipamọ lagdo ni a kọ lari óṣu august ọdun 1977 ati óṣu july ọdun 1982 lati ọwọ óṣiṣè ilẹ china engineer ati labira cameroon ilè iṣẹ to mojuto ìṣẹ naa ni china intern... |
federal university gashua federal university gashua fugashua jẹ ile-ẹkọ giga ti o da ni ipinle yobe ariwa ila-oorun naijiria o jẹ ile-ẹkọ ẹkọ ati iwadi ti o n wa lati yanju awọn iwulo lẹsẹkẹsẹ ti awujọ ati fun gbogbo eniyan ni aye lati ni imọ ile-ẹkọ giga ti dasilẹ ni ọdun 2013 nipasẹ alakoso goodluck jonathan eyi ni a... |
the looming fogi looming fog jẹ aramada akọkọ ti 2006 nipasẹ onkọwe naijiria rosemary esehagu itan naa tẹle igbesi aye ọmọ ibalopọ kan bi wọn ṣe n tiraka lati gbe ni abule ti iṣaaju ijọba ijọba ni nigeria ti o ka aiṣedeede si ohun irira nipasẹ olutọpa orukọ ti ko ni orukọ ati alatumọ ọkan di mimọ ti awọn ọmọ ẹgbẹ miira... |
omenuko omenuko nipasẹ pita nwana nipasẹ oniṣowo kan gbẹnagbẹna jẹ aramada akọkọ ti a kọ ni ede igbo ti iwe naa si ṣe aṣeyọri pupọ laarin awọn ọmọ igbo iwe naa so itan igbesi aye oloṣelu naa igwegbe odum aro igbo ti o lọ si arondizuogu ti a kọ ni 1933 o gba ẹbun kan ninu idije ti international african institute ti nṣe ... |
zahra oluwa afẹfẹ zahrah the windseeker jẹ aramada irokuro agbalagba ọdọ ati aramada akọkọ ti onkọwe ara ilu amẹrika nnedi okorafor ti a ṣejade ni oṣu kẹsan ọdun 2005 o ṣafikun awọn arosọ ati itan-akọọlẹ ati aṣa ti nigeria o jẹ olubori ti 2008 wole soyinka prize for literature in africa idite iwe aramada naa waye ni ij... |
nigeria hockey federation nigeria hockey federation nhf jẹ́ àjọ tó ń ṣàkóso eré bọ́ọ̀lu aláfigigbá orí pápá field hockey ní orílẹ̀ èdè nigeria ó wà ní abẹ́ ihf international hockey federation àti ahf african hockey federation olú iléeṣẹ́ nhf wà ní abuja nigeria engineer obadiah simon nkom ní ààrẹ nhf tí chimezie asiegb... |
anthills of the savannah anthills of the savannah jẹ aramada 1987 lati ọwọ onkọwe naijiria chinua achebe o jẹ iwe-kikọ karun rẹ ti o kọkọ ṣejade ni united kingdom ni ọdun 21 lẹhin ti achebe ti tẹlẹ a man of the people in 1966 ati pe o jẹ pe o ti sọji orukọ rẹ ni britain aṣepari fun 1987 booker prize for fiction anthill... |
esie musium nigeria museum esiẹ musium jẹ ile ọnọ ni esiẹ ipinle kwara ni orile ede nàìjíríà esie je ilu igbomina ni ijoba ibile irepodun lga ni ilu kwara esiẹ musium ni ile ọnọ akọkọ ni orile ede nigeria ti a da silẹ ni ọdun 1945 lati gbe ọkan ninu awọn iṣura nla julọ ti a ti fi silẹ fun ẹda eniyan awon ere esie ile ọ... |
esie musium |
salman mazahiri ọ̀gbẹ́ni salman mazahiri tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1946 ó kú lógúnjọ́ oṣù keje ọdún 2020 jẹ́ ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè india tí ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí gíwá ilé-ẹ̀kọ́ gíga mazahir uloom jadeed ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́ life wọ́n bí mazahiri lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1946 nígbà tó wà lọ́mọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún... |
hussaini abdu hussaini abdu hussaini abdu jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nípa ètò ọrọ̀ ajé àti ẹ̀kọ́ agbófinró ní ilé ẹ̀kọ́ gíga nigerian defence academy ní kaduna iṣẹ-ṣiṣe rẹ ni ọpọlọpọ awọn iṣẹ ṣiṣe lọpọlọpọ pẹlu igbekalẹ igbekalẹ ati awọn atunwo ominira igbero ilana ati awọn ijumọsọrọ kariaye ni gbogbo afirika ati latin america o... |
mufti abdul razzaq mufti abdul razzaq tí orúkọ àdàpè rẹ a máa jẹ́ abdul razzaque khan lati 13 august 1925 títí dé 26 may 2021 jẹ́ onímọ̀ ẹ̀kọ́ èsìn islamu ati ọmọ india mufti tí ó tun jẹ́ ajìjàgbara fun òmìnira ilẹ̀ india ti o sin orílẹ̀ ede rẹ̀ ní ipò kẹsan akọ̀we àgbà fun jamiat ulama-e-hind òun nígbà ayé rẹ̀ ni igbá... |
idanre forest reserve ibi ipamọ igbo idanre wa ni agbegbe ijọba ibilẹ idanre ni ipinlẹ ondo ti naijiria ni apa gusu iwọ-oorun orilẹede naa ijọpọ kariaye yii fun itoju ti iseda ti a yan iyasọtọ iseda ni wiwa ó jẹ́ igbó kìjikìji ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ tí ó ga ní 10 sí 400 mítà ibi ipamọ igbo idanre nfunni ni idapọ alailẹgbẹ ti ẹwa... |
hussain abdul-hussain hussain abdul-hussain arabic حسين عبدالحسين jẹ ẹlẹgbẹ iwadi ni foundation fun idaabobo ti awọn ijọba tiwantiwa agbari ti kii ṣe alaiṣedeede ni washington o ṣiṣẹ tẹlẹ bi oloye ajọ washington ti iwe iroyin kuwaiti al rai eyiti o jẹ al rai alam tẹlẹ hussain abdul-hussain tun ṣiṣẹ fun ile-igbimọ amẹri... |
hussain haroon a scion ti idile haroon o jẹ oniṣowo kan alakitiyan awujọ ati agbọrọsọ apejọ sindh tẹlẹ kan ti o jẹ ọmọ ẹgbẹ igbimọ ti ọpọlọpọ awọn ile-ẹkọ eto-ẹkọ awọn ẹgbẹ ere idaraya ati awọn ẹgbẹ alaanu igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ hussain haroon jẹ ọmọ saeed haroon arakunrin agba ti hameed haroon ati ọmọ-ọmọ sir abdull... |
nàìjíríà-ikowo bank bank ile-ifowopamọ ikowọle ilu okeere ti ilu naijiria nexim jẹ ile-iṣẹ kirẹditi okeere ti ilu okeere ni nigeria ti iṣeto ni ọdun 1991 ninu iṣẹ rẹ nexim fojusi lori idagbasoke ati imugboroja awọn apakan ti kii ṣe epo ti eto-ọrọ aje orilẹ-ede naijiria pẹlu ero lati dinku igbẹkẹle orilẹ-ede naa lori gb... |
hussain abdulrahman hussain abdulrahman larubawa حسين عبد الرحمن ti a bi 31 oṣu kẹwa ọdun 1994 jẹ agbabọọlu emirati ti o nṣere bii agbabọọlu fun ajman iṣẹ-ṣiṣe dubai hussain abdulrahman bẹrẹ iṣẹ rẹ ni dubai ati pe o jẹ ọja ti eto ọdọ dubai lori 10 may 2014 hussain abdulrahman ṣe akọrin akọkọ rẹ fun dubai lodi si al-nas... |
ile-iṣọ millennium abuja ise agbese ile-iṣọ millennium ati cultural jẹ ọkan ninu awọn iṣẹ akanṣe ni central district ti olu ilu naijiria ti abuja ni o jẹ ọna atọwọda ti o ga julọ ni abuja ile-iṣọ ti manfredi nicoletti ṣe apẹrẹ ati pe o jẹ apakan ti ile-iṣọ orilẹ-ede naijiria ti o tun pẹlu ile-iṣẹ asa ilu naijiria ile-i... |
adamawa state polytechnic adamawa state polytechnic jẹ ile-ẹkọ ẹkọ ile-ẹkọ giga ni yola ipinle adamawa nigeria o ti dasilẹ ni ọdun 1991 nipasẹ iṣọpọ ti ile-ẹkọ giga ti awọn ẹkọ ibẹrẹ yola ati ile-iṣẹ idagbasoke oṣiṣẹ numan polytechnic tuntun n pese awọn eto iwe-ẹkọ giga ti orilẹ-ede ni imọ-ẹrọ kọnputa awọn iṣiro iṣiro-... |
mazahir uloom jadeed islamic seminary in india ọ̀gbẹ́ni mazahir uloom jadeed jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀sìn mùsùlùmí ní saharanpur lórílẹ̀-èdè india ó yapa láti ara ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀sìn mùsùlùmí mazahir uloom tí ó sì dá dúró lọ́dún ó máa ń ṣe àtẹ̀jáde ìwé jọ́nà kan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní mazāhir-e-uloom títí di oṣù kẹta ọdú... |
audu bako ilé ìwé nina àgbà ìgbàlódé ilé ìwé audu bako ti dambatta kano state nigeria ṣe awards diplomas ni imọ ati iṣẹ-ṣiṣe koko fun arin-ipele eniyan orukọ rẹ ni orukọ audu bako gomina tẹlẹ ti ipinlẹ naa == ọdun 2002 ni wọn ti da kọlẹji naa silẹ ati pe ipinlẹ kano jẹ ohun ini ati ti iṣakoso o jẹ ifọwọsi lati funni ni... |
kí ni ilé-ẹ̀kọ́ 2015 book by ebrahim moosa kíni madrasa jé ìwé tí a ti owó ebrahim moosa tí ó jé onímò ìjìnlè nínú èsìn islam tí ó sì jé olópolo pípé èdá ìwé yii je àkójopò ìtàn ayé ìgbenuso àyèwò èyà ènìyàn àti ìtàn ìgbà pípé tí ó sì n fún ni ní ìwòye gégé bíi ti eni tí ó wà nínú deobandi madrasas nínú àdáyébá-ile kék... |
lateef olufemi okunnu nigerian lawyer lateef olufemi okunnu tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún òṣù kejì ọdún 1933 jẹ́ agbẹjọ́rò àgbà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti alága àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn university of agriculture makurdi ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí lateef okunu ní ọjọ́ kọkàndínlógún òṣù kejì ọdún 1933 ní ìlú èk... |
syed ahmad dehlvi indian muslim scholar ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ ahmad saeed dehlavi ọ̀gbẹ́ni syed ahmad dehlvi tí wọ́n tún lè kọ báyìí sayyid aḥmad dihlawī tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kìíní ọdún 1846 ó kú lọ́jọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1918 jẹ́ onímọ̀ ẹ̀sìn mùsùlùmí onímọ̀ èdè àti ọ̀rọ̀ onímọ̀ òye onímọ̀ ẹ̀kọ́ ọmọ bíb... |
sayyid mumtaz ali sayyid mumtaz ali deobandi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1860 tí o sì papòdà ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹfà ọdún 1935 ó jẹ́ ọ̀mọ̀wé musulumi sunni ará ìlu india àti alágbàwí ti ètò àwọn obìnrin ní òpin ọ̀rúndún 19th ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ilé-ìwé ti darul uloom deoband ìwé rẹ̀ huquq-e-n... |
yasin mazhar siddiqui yasin mazhar siddiqui tí a mọ̀ sí yasin mazhar siddique nadvi 26 december 1944 títídé 15 september 2020 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè india onimọ̀ ẹ̀kọ́ ti musulumi sunni àti onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìwádí ìtàn tí ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bí alakoso ẹ̀ka ìmọ̀ nípa islam ti ilé ẹ̀kọ́ giga ti mùsùlùmí ní aligarh yasin mazhar si... |
sayyid muhammad abid sayyid muhammad abid tí a tún mọ̀ sí hāji abid hussain 18341912 jẹ́ ọ̀mọ̀wé mùsùlùmí ará íńdíà kan tó dá darul uloom deoband sílẹ̀ ó jẹ́ igbákejì alákoso ti darul uloom deoband fún ìgbà mẹ́ta ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ abid hussain ni a bí ní ọdún 1834 ní deoband mughal india nínú ìdílé tí ó ní ìr... |
nilofer khan nilofer khan jẹ́ ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ india àti òǹkọ̀wé tí ó ńṣe ìránṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ bí igbákejì-alákoso ti fásítì kashmir o ti yan obinrin akọkọ igbakeji-alakoso ti university ni 19 may 2022 iṣẹ́ nilofer khan ti ṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀ bí olórí ìṣesí àwọn ọmọ ilé-ìwé dean ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga fásítì ti kashmir ku ó jẹ́ obìnr... |
syed ahmad hashmi syed ahmad hashmi ọjọ́ kẹta-dín-lógún oṣù kìíní ọdún 1932 sí ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 2001 jẹ́ ọmọ ilé-ìwé mùsùlùmí ará ìlú india àti olóṣèlú tí ó ṣiṣẹ́ bí akọ̀wé gbogbogbò kéje ti jamiat ulama-e-hind àti alága ti ìgbìmọ̀ àwọn ohun èlò ìrìn-àjò ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti rajya sabha tẹ́lẹ̀ ilé gíga ti ilé-... |
abdul ghani azhari indian muslim scholar 19222023 abdul ghani azhari 1922 19 january 2023 tí a tún mò sí abdul ghani shah al-shashi jé omo ilè india tí o jé oní ìmò ìjìnlè àti akoìtàn tí ó se isá gege bíi òjògbón àgbà ní ilé-èkó gíga university of kashmir ní èka-isé èdè lárúbáwá ó jé akeko jade ní darul uloom deoband m... |
what is a madrasa |
mahfoozur rahman nami indian muslim scholarmahfoozur rahman nami may 1911 17 november 1963 jé mùsùlùmí onímò ìjìnlè olósèlú àti ònkòwé a bíi ní osù karùn odún 1911 nami jé akékò jáde ilé-ìwé jamia miftahul uloom àti darul uloom deoband ó se ìdásílè madrasa nūr-ul-ulūm àti azad inter college ní bahraich ó kú ní ojó ketà... |
nadwatul ulama council of muslim scholars nawatul ulama jẹ igbìmọ ti awọn ónimọ nipa ẹsin musulumi ti ilẹ india ti a da silẹ ni ọ̀dun 1893 ni kanpus alabóju akọkọ fun ìgbìmọ naa ni muhammad ali mungeri ti bilal abdul hai hasani nadwi jẹ̀ alabójutó isin ìgbìmọ naa da ilè ẹkọ darul uloom nadwatul ulama silẹ̀ ni ọjọ kẹrin... |
habibur rahman khairabadi indian mufti habibur rahman khairabadi o tumọ si mufti habībur rahmān wọn bini ọjọ kọkanla óṣu august ọ̀dun 1933 jẹ̀ ọnimọ ẹsin musulumi ati adajọ ti mufti darul uloom deoband arakunrin naa jẹ alumnus ti darul uloom mau mazahir uloom ati ilè iwè giga musulumi ti aligarh awọn iwè rè ni ofin did... |
abdul hai arifi pakistani islamic scholar abdul hai arifi 189827 march 1986 jé òmòwé mùsùlùmí omo ilè pakistani àti olùtóni sufi ti ìlànà chishti order ó jé omo èyìn ashraf ali thanwi ó se ìtèjáde àwon ìwé bíi uswah rasool-e-akram àti ikú àti ogún ó s'isé gégé bíi ààre ti darul uloom karachi fún bíi odún méwà arifi jé ... |
nadwatul musannifeen indian research institution ilé-ìwé nadwatul musannifeen jẹ́ gbọ̀ngán a ṣèwádìí àti ilé aṣètẹ̀jáde-ìwé ní delhi àwọn ọ̀mọ̀wé ọ̀gbẹ́ni atiqur rahman usmani hamid al-ansari ghazi hifzur rahman seoharwi àti saeed ahmad akbarabadi ni wọn dìjọ dá a sílẹ̀ lọ́dún 1938 ìtàn àwọn ọ̀mọ̀wé atiqur rahman usman... |
syed anwarul haq haqqi ọ̀gbẹ́ni syed anwarul haq haqqi tí a tún mọ̀ sí s a h haqqi tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún oṣù kìíní ọdún 1922 ó kú lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 2010 jẹ́ ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè india tí ó fìgbà kan jẹ́ olórí ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìṣèlù ní aligarh muslim university fún ọdún ogún ọdún ó jẹ́ àbúrò sí abrarul... |
akbar shah khan najibabadi akbar shah khan najibabadi 1875 ọjọ kẹwa may 1938 jẹ ónimọ itan sunni ẹ̀lẹsin musulumi ti ilẹ̀ india to kọ tarikh-e-islam ni iwọn didun mẹta itan ìgbèsi àye akbar shah khan najibabadi najibabadi ni wọn bi ni ọdun 1875 ni najibabad bijnor united provinces ti british india arakunrin naa bẹrẹ iṣ... |
nasir ahmad qasmi nazir ahmad qasmi wọ́n bí ní ogunjọ́ oṣu kẹ́fà 1964 jẹ́ onímọ̀ islam ti kashmiri sunni ati juri tí o jẹ mufti àgbà fun darul uloom raheemiyyah ó jẹ́ akẹkọọ jade ni darul uloom deoband ati imārat-e-sharia o jẹ́ ọ̀kan nínù àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ alabójúto ofin gbogbo mùsùlùmí ní india àti akọ̀wé àgbạ fú... |
muhammad sahool bhagalpuri muhammad sahool bhagalpuri tí ó papòdà ní ọdún 1948 jẹ́ ọmọ india onímọ̀ ẹ̀sìn islam àti oní juri tí ó jẹ́ mufti àgbà karun-un ti darul uloom deoband ìtàn àkọsílẹ̀ muhammad sahool bhagalpuri ni wọ́n bí ní puraini bhagalpur sí inú ẹbí mùsùlùmi ìran uthman sahool kọ́ ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ nínú ilé ó... |
ojú ọjọ́ oju-ọjọ jẹ apẹrẹ oju-ọjọ igba pipẹ ni agbegbe kan deede ni aropin ju ọdun 30 lọ ni lile diẹ sii o jẹ itumọ ati iyipada ti awọn oniyipada oju ojo lori akoko kan ti o lọ lati awọn oṣu si awọn miliọnu ọdun diẹ ninu awọn oniyipada oju ojo ti o wọpọ ni iwọn otutu ọriniinitutu titẹ oju aye afẹfẹ ati ojoriro ni ọna t... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.