raw_text
stringlengths
2
128k
george henry white george henry white je oloselu ara amerika ati asoju ni ile asoju amerika tele
frederica wilson frederica wilson jẹ́ olóṣèlú ará amẹ́ríkà àti aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ asojú amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀
albert wynn albert russell wynn ọjọ́ìbí september 10 1951 jẹ́ olóṣèlú ará orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà àti aṣojú ní ilé àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀ fún ìpínlẹ̀ maryland láti ọdún 1993 di ọdún 2008
andrew young andrew young je oloselu ara amerika ati asoju ni ile asoju amerika tele
phylicia rashad phylicia rashād oruko abiso phylicia ayers-allen june 19 1948 je osere ati akorin ara american to gba ebun tony o gbajumo fun ere re gegebi clair huxtable ninu ere telifisan the cosby show
phylicia rashād
ìlàoòrùn timor
àríwá kòréà
ram narayan ram narayan híndì iast rām nārāyaṇ ojoibi 25 december 1927 nigba miran ti won unpe ni pandit je olorin ara india to mu irinse orin sarangi gbajumo bi irinse orin agbo adalu ninu orin ogbologbo hindu to si gbajumo kariaye bi onilu sarangi narayan je bibi ni udaipur o si ko lati ta sarangi lati igba kekere
coat of arms of cyprus
flag of england
flag of dominica
àsìá ilẹ̀ dominika
àsìá ilẹ̀ dominica
flag of the dominican republic
àsìá ilẹ̀ dominican republic
dómíníkì olómìnira
àrubà
flag of aruba
àsìá ilẹ̀ aruba
octavia butler octavia estelle butler june 22 1947 february 24 2006 je ara amerika olukowe itan-aroso sayensi o gba ebun hugo ati nebula ni 1995 o di olukowe itan aroso sayensi akoko to gba igbowo macarthur
oṣù kẹfà 22
oṣù kejì 24
george carlin george denis patrick carlin may 12 1937 june 22 2008 je ara amerika alawada ori itage ayewo awujo osere ati olukowe to gba ebun grammy marun fun awon awo awada re
oṣù kàrún 12
peggy ashcroft peggy ashcroft ni a bini ọjọ ọjọ kèjilèèlóógun ọdun 1907 ti osi ku ni ọjọ kẹfa dinlóógun ọdun 1991 peggy jẹ óṣèrè lóbinrin ti ilẹ gẹẹsi to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbesi àyè àrabinrin naa ashcroft ni a bini croydon surrey fun violetta maud 1874-1926 ati william worsley ashcroft ...
mary astor mary astor je òṣérébinrin tí wọ́n bí lucile vasconcellos langhanke ní ọjọ́ keta oṣù karun ọdún 1906 je òṣérébinrin orílẹ̀ edè america to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo nígbà ayé re
fay bainter fay okell bainter december 7 1893 april 16 1968 jẹ́ òṣèré orí ìtàgè ni orílé èdè améríkà óò gbà àmi ẹ̀yẹ ni akádẹ́mì fún ẹni tí ó ń ṣe amúgbálẹ́gbẹ́ fún olu òṣèré inú eré tí àkọlé rẹ ń ni jezebel ní ọdún 1938 ó sí gbà àmi ẹyẹ irawọ ní hollywood walk of fame ní ọdún na fay bainter jẹ́ òṣèrée tó gba ẹ̀bùn aká...
ethel barrymore ethel barrymore je óṣèrè lóbinrin ilẹ america ti a bini óṣu august 1879 to si ku ni óṣu june ọdun 1959ethel barrymore jẹ óṣèrè lóbinrin ti stage screen pẹlú radio to si ṣisẹ fun ọdun mẹfa igbesi àyè àrabinrin naa ethel ni a bi fun óṣèrè lọkunrin maurice barrymore ati óṣèrè lóbinrin georgiana drew ethel ...
kim basinger american actress kim basinger je osere to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àyè áràbinrin naa basinger ni a bini athens georgia ni ọdun 1953 fun an lee 1925-2017 ati donald wade 1923-2016 basinger jẹ alumna ti william esper studio fun performing arts ni manhattan new york city ki óṣè...
anne baxter anne baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kaarun ọdún 1923 tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kéjììlá oṣù kéjììlá ọdún 1985 ó jẹ́ òṣèrébinrin to gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo nígbà áye rẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ anne baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kaarun ọdún 1923 ní ìlú michigan indiana si idìlé c...
juliette binoche french actress artist and dancer born 1964juliette binoche tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹ́ta ọdún 1964 jẹ́ òṣèrè àti oníjó faransé ó ṣe àfihàn ní fíìmù bíi ọgọ́ta tí wọ́n pè é sí àti wí pé ó tún jẹ́ ẹni tó gba àwọn àwọ́ọ̀dù bíi àwọ́ọ̀dù akadẹ́mì british academy film award silver bear cannes film fe...
cate blanchett cate blanchett je osere to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo
alice brady alice brady orúkọ àbísọ rẹ ni mary rose brady ọjọ́ ìbí je november 2 1892 si october 28 1939 jẹ́ òṣèré kàn ní orílé èdè améríkà tí ì bẹrẹ iṣé náà ni àkókò tí wọn ń pé ní silent era èyí tí o padà di àsìkò tí wọn pè ní sound film/talkies o sìse títí di oṣù mẹ́fà kí ó pàdúnu èmi rẹ sórí ààrùn jẹjẹrẹ cancer ní ...
jennifer connelly american actress born 1970 jennifer connelly je osere to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àyè àràbinrin naa connelly ni à bisi cairo new york ni catskill mountains óṣèrè lóbinrin naa jẹ ọmọ òbinrin ilene dealer ti antique ati gerard karl connelly óluṣẹda àṣọ baba jennifer jẹ ọm...
penélope cruz spanish actress penélope cruz jẹ óṣere lobinrin ilẹ spanish ti a bini ọjọ 28 óṣu april ni ọdun 1974 óṣere lobinrin naa gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbèsi àyè àràbinrin naa cruz ni a bi si alcobendas spain fun encarna sàchez ẹni tin ṣè irun ati eduardo cruz olutaja ati mechanic óṣere ...
jane darwell american actress 18791967 jane darwell tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ patti woodard tí wọ́n bí ní oṣù kẹwàá ọjọ́ karùn-ún ọdún 1879 tí ó sì kú ní oṣù kẹ́jọ ọjọ́ kẹtàlá ọdún 1967 jẹ́ òṣèrè amẹ́ríkà lórí orí-ìtàgé fíìmù àti tẹlẹfísọ̀n ó ṣe àfihàn ní fíìmù bí ọgọ́rùn-ún ní fún àsìkò sẹ́ńtúrí díẹ̀ ó jẹ́ òṣèrè tó gba e...
geena davis geena davis jẹ óṣèrè lóbinrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbèsi àyè àrabinrin naa davis ni a bini ọjọ kèjilèèlogun óṣu january ni ọdun 1956 si ilu wareham massachusettsiyà óṣèrè lóbinrin naa lucille jẹ ẹni to ran ólúkọ lọwọ ti baba rẹ william f davis jẹ civil engineer ati deacon ti...
judi dench english actress born 1934 judi dench je óṣèrè lóbinrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àyè àràbinrin naa dench ni à bini heworth area ti york ni ọdun 1934 fun eleanora olive ati reginald arthur dench to jẹ dokita 1897-1964 iya óṣere lóbinrin naa wa lati iran irish ti a si bisi dub...
sandy dennis sandra dale dennis oṣù kẹrin ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n ọdún 1937 sí oṣù kẹta ọjọ́ kejì ọdún 1992 jẹ́ òṣèré obìnrin ti ilẹ̀ amẹ́ríkà ó ṣe àṣeyọrí nínú fíìmù tó gbé e jáde splendor in the grass ọdún 1961 fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú fíìmù eré dírámà àpanilẹ́rìn-ín who's afraid of virginia woolf ọdún 1966 ó gba ẹ̀bùn àmì ẹ...
olympia dukakis olympia dukakis ni wọ́n bí ní ọjọ́ kéjììlélógún oṣù kẹfà ọdún 1931 tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kìníí oṣù karun ọdún 2021 jẹ́ òṣèrébinrin orílẹ̀ èdè america to gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo nígbà ayé rẹ̀ ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí olympia dukakis sí lowell massachusetts lọ...
patty duke anna marie patty duke tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrinlá oṣù kejìlá ọdún 1946 tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kokandinlogbon oṣù keta ọdún 2016 je òṣérébinrin orílẹ̀ èdè america to gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo golden globe awards lẹ́mejiì ọtòtò primetime emmy awards lemeta nígbà áye rẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀p...
brenda fricker brenda fricker tí a bí ní ọjọ́ kẹta-dín-lógún ọdún 1945 jẹ́ òṣèré irish kan tí iṣẹ́ rẹ̀ ti kọjá ọgbọ̀n ọdún ní orí ìtàgé àti lórí ojú ìwòrán ó ti farahàn ní fíìmù àti àwọn ipò tẹlifísàn tó ju ọgbọ̀n lọ ní ọdún 1990 ó di òṣèré irish àkọkọ́ láti gba ààmì-ẹ̀rí ilé-ẹ̀kọ́ gíga kan tí ó gba ẹ̀bùn náà fún òṣèré...
ruth gordon ruth gordon ti a bí ní oct 30 1986 ti ósì fi ayé sílè ní august 28 1985 jé òsèrébìnrin àti olùko òsèré omo orílè-èdè amerika ó gba ebun akademi fún obinrin osere keji didarajulo ó bèrè isé òsèré ní odun 1915 ìgbàyen ni ó jé omo odún kandinlogun apere àwon eré to sere nínú won ni rosemary's baby 1968 what ev...
gloria grahame american actress 19231981 gloria grahame je óṣèrè lóbinrin ati akọrin ilẹ america to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àyè àrabinrin naa grahame ni à bisi los angeles óṣèrè lóbinrin naa ni à tọ ni ilana methodist baba gloria reginald michael bloxam jẹ architect ti ilẹ èdè gẹẹsi ati...
lee grant lee grant orúkọ àbísọ ni lyova haskell rosenthal tíwọ́n bí ní october 31 ní àárín 1920 jẹ́ òṣèré ilé améríkà olùdarí eré àti ẹni tí ó ń ṣe iṣé documentary eré àkọkọ rẹ ní èyí tí o ṣe ọmọde tí ń fẹ́wọ́ nínú eré detective story tí william wyler ṣe adarí eré náà ni 1951 àwọn tí wọn sì kópa náà ní kiri douglas àt...
marcia gay harden marcia gay harden ni wọ́n bí ní ọjọ́ kerìnlá oṣù kẹjo ọdún 1959 jẹ́ òṣèrébinrin orílẹ̀ èdè america tó ti gba orisirisi ebún bi ebun akademi ati tony award ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí sí la jolla california omo-bíbi beverly harden née bushfield harden parí ní ile eko girama ti surrattsville c...
goldie hawn american actress goldie hawn je óṣèrè lóbinrin ti ilẹ america to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àyé àrabinrin naa hawn ni à bini washington dc fun laura ati edward rutledge hawn óṣèrè lóbinrin naa ni à sọ orukọ rẹ latara aunt iya rẹ baba goldie ni presbyterian ti german ti iran rẹ ...
eileen heckart american actress 19192001 eileen heckart ni a bini óṣu kẹta ọdún 1919 to sì kú ní óṣù kejìlá ọdún 2001 ti jẹ óṣèrè lóbinrin to siṣẹ fun ọgọta ọdun igbèsi àyè àràbinrin naa heckart ni a bi si ọdọ anna eileen herbert ni ilú columbus ohio orukọ iya óṣèrè lóbinrin naa njẹ esther ti baba rẹ si njẹ leo herbert...
wendy hiller english stage and film actress 19122003 dame wendy margaret hiller ni a bini ọjọ karun dilogun óṣu august ni ọdun 1912 ti o si ku ni ọjọ kẹfa dilogun óṣu may ni ọdun 2003 15 august 1912 14 may 2003 jẹ óṣèrè óritage èdè gẹẹsi ti o si tin ba iṣẹ naa bọ lati ọgọta ọdun wendy duró gẹgẹbi óṣèrè oritage pẹlu gbo...
celeste holm celeste holm jẹ óṣèrè lóbinrin ti ere oritage filmu ti ilẹ america ti a bini óṣu april ọdun 1917 to si ku ni óṣu july ọdun 2012 igbèsi àyè àrabinrin naa celeste ni a bisi ilú manhattan to si jẹ ọmọ ẹyọkan ṣoṣo ti iya rẹ jean parke ólúkọwè ati baba rẹ theodor holm óniṣowo bi igbèyawọ holm akọkọ waye ni ọdun...
jennifer hudson american singer and actress born 1981 jennifer hudson je osere lóbinrin ati akọrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àràbinrin naa hudson ni a bini óṣù september ọdun 1981 ni chicago illinois jennifer ni a tọ ni ilana baptist ni englewood nigba ti jennifer pè ọmọ ọdun meje ni ó...
josephine hull marie josephine hull née sherwood tí a bí ní oṣù kìíní ọjọ́ kẹta ọdún 1877 sí oṣù kẹta ọjọ́ kejìlá ọdún 1957 jẹ́ onítàgé ilẹ̀ amẹ́ríkà àti òṣèré obìnrin fíìmù tí ó sì jẹ́ ìtọsọ́nà àwọn eré ó ní àṣeyọrí àádọ́ta ọdún lórí ìtàgé nígbà tí ó ń gbé àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tó ti gba ìdánimọ̀ lọ inú fíìmù ó gba ẹ̀bùn àmì ...
linda hunt lydia susanna linda hunt tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún 1945 je òṣérébinrin orílẹ̀ èdè america tó gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí linda hunt ní lọ́jọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún 1945 sí morristown new jersey sínú idìlé raymond davy hunt ati elsie doying...
kim hunter kim hunter tí a bí janet cole oṣù kọkànlá ọjọ́ kejìlá ọdún 1922 sí oṣù kẹsán-án ọjọ́ kọkànlá ọdún 2002 jẹ́ òṣèré ìtàgé fíìmù àti tẹlifísàn ó ṣe àṣeyọrí fún ìṣàfihàn stella kowalski nínú ìṣelọ́pọ̀ àtilébá ti a streetcar named desire ti tennessee williams èyí tí ó àtúnwí fún àṣàmúdọ́gba fíìmù ọdún 1951 tí ó sì...
anjelica huston anjelica huston tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjoo oṣù keje ọdún 1951 jẹ́ òṣèré orí ìtàgè oludari fiimu ti orílé èdè améríkà ó je osere to gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí anjelica huston lọ́jọ́ kẹjoo oṣù keje ọdún 1951 si ile-iwosan ti the cedars of lebanon ...
angelina jolie angelina jolie tí orúkọ àbìsọ rẹ̀ ń jẹ́ angelina jolie voight ní kíkún wọ́n bi ní ọjọ́ kẹrìn oṣù kẹfà ọdún 1975 ó jẹ́ òṣerébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà bákan náà ni ó tún jẹ́ olótùú eré àti ẹlẹ́yinjú àánú ó ti gba àmì ẹ̀yẹ oríṣiríṣi bí ebun akademi àti golden globe awards mẹ́ta léra wọn òun ni wọ́n kà ...
shirley jones american singer actress shirley jones ni a bini ọjọ 31st óṣu march ni ọdun 1934 ti o si jẹ osere lobinrin ati akọrin ilẹ amẹrica igbesi ayè arabinrin naa shirley ni a bini ilẹ charleroi pennsylvania fun awọn obi ijọ methodist marjorie ati paul jones nibi ti baba rẹ ti jẹ oludari ilè iṣẹ ọti ti jones óṣèrè...
lila kedrova elizaveta lila nikolaevna kedrova russian елизавета лиля николаевна кедрова oṣù kẹwàá ọjọ́ kẹsan ọdún 1909 sí oṣù kejì ọjọ́ kẹrin-dín-lógún ọdún 2000 jẹ́ òṣèré obìnrin faransé tí wọ́n bí láti ìran russia ó gba ẹ̀bùn ẹ̀yẹ fún òṣèré àtìlẹ́yìn obìnrin tó dára jùlọ fún zorba the greek ọdún 1964 àti àmì ẹ̀yẹ to...
cloris leachman cloris leachman ni a bini óṣu april ọdun 1926 to si ku ni óṣu january ọdun 2021 cloris jẹ óṣèrè lóbinrin ati alawada to si ṣiṣẹ fun ọgọrin ọdun igbèsi àyè arabinrin naa leachman ni a bi fun cloris ati berkeley claiborne si ilu des moines iowa cloris gba ẹkọ ọfẹ lati kẹẹkọ ni studio óṣèrè lọkunrin ni new...
melissa leo american actressmelissa chessington leo wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kẹsàn-án ọdún 1960 jẹ́ ọ̀sèrè amẹ́ríkà ó gbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọ́ọ̀dù bí àwọ́ọ̀dù akadẹ́mì primetime emmy award golden globe award screen actors guild award àti critics' choice awards méjì lẹ́yìn àfihàn ẹ̀ ní àwọn eré lórí tẹlẹfísọ̀n àti fíìmù 1...
mercedes mccambridge american actress 19162004 mercedes mccambridge ni à bini ọjọ kẹfadinlógun óṣu march ọdun 1916 ti ó si ku ni ọdun 2004 jẹ óṣèrè lóbinrin ti radio stage film ati television ilẹ america to gba ebun akademi bi obinrin osere keji to dara ju lo igbèsi àyè àràbírin naa mccambridge ni a bini jolliet illino...
hattie mcdaniel hattie mcdaniel june 10 1895 october 25 1952 je óṣèrè lobinrin omo afrika amerika akoko to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ìgbèsi àyé àràbinrin naa mcdaniel jẹ ọmọ to kèrèju ninu awọn ọmọ mẹtala ti awọn óbi rẹ bi óṣèrè lóbinrin naa ni à bi ni ọdun 1893 fun awọn ti akó lèru susan holber...
dorothy malone dorothy malone tí a bí mary dorothy maloney ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1924 sí ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lógún oṣù kìíní ọdún 2018 jẹ́ òṣèré ará ilẹ̀ amẹ́ríkà kan iṣẹ́ ìṣe fíìmù rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1943 àti ní àwọn ọdún ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ó ṣe àwọn ipá kékeré ní pàtàkì jùlọ ní àwọn b-movies pẹ̀lú èrò láti gba i...
mo'nique monica imes ojoibi december 11 1967 to gbajumo bi mo'nique je àlawada ati óṣere lóbinrin ara amerika to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbèsi àyè arabinrin naa mo'nique ni a bini woodlawn baltimore county ni maryland óṣere lobinrin naa jẹ ọmọ alice imes engineer ati steven imes ólúbadamọran ...
rita moreno puerto rican singer dancer and actress born 1931 rita moreno ni a bini ọjọ kọkanla óṣu december ni ọdun 1931 ti ósijẹ ónijó akọrin ati óṣere rita gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbesi aye arabinrin naa àbi rita si humacao puerto rico fun rosa maria ólúran àṣọ lobinrin ati francisco josé a...
tatum o'neal american actress tatum o'neal jẹ olukọwe ati óṣere lobinrin ilẹ america ti a bini ọjọ karun óṣu november ni ọdun 1963 igbesi ayè arabinrin naa tatum ni wọn bisi los angeles california fun óṣèrè ryan o'neal ati joanna moore awọn obi óṣere lobinrin naa pinya ni ọdun 1967 iya tatum ku ni ọmọọdun mẹta lelọgọta...
anna paquin anna paquin tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kéje ọdún 1982 jẹ́ òṣèrébinrin orílẹ̀-èdè new zealand to gba ebun akademi obinrin osere keji didarajulo ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí anna paquin sí winnipeg manitoba o jẹ́ ọmọ mary paquin née brophy ati brian paquin paquin lọ sí ile ẹ́kọ́ alakọbréẹ̀ r...
estelle parsons american actress estelle parsons ni a bini óṣu november ọdun 1927 to jẹ óṣèrè lóbinrin ólórin ati oludari ti stage igbesi ayè àrabinrin naa estelle ni a bisi ilè iwósan ti lynn iya óṣèrè lóbinrin naa elinor ingeborg ti a bini ilẹ sweden ati baba rẹ eben parsons to wa lati iran èdè gẹẹsi parsons fẹ ólukọ...
katina paxinou katina paxinou je òṣèrébìnrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo
vanessa redgrave british actress vanessa redgrave je ọmọ óṣèrè lọkunrin sir michael regrave ati óṣèrè lobinrin rachel kempson ti a bini ọjọ ọgbọn óṣu january ni ọdun 1937 arabinrin naa jẹ osere to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbesi aye arabinrin naa vanessa kẹkọ ni ilè iwè tadalẹ fun awọn ọmọ obin...
donna reed american actress 19211986donna reed wọ́n bí donna belle mullenger ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1921 ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní ọdún 1986 ó jẹ́ òṣèrè amẹ́ríkà ìgbà tó fi ṣe eré lọ fún bíi ogójì pẹ̀lú àwọn ipa àti akitiyan rẹ̀ ní fíìmù tó ju ogójì lọ àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ dáadáa fún ipa...
anne revere anne revere oṣù kẹfà ọjọ́ márùn-ún-dín-lọ́gbọ̀n-lọ́gbọ̀n ọdún 1903 sí oṣù kejìlá ọjọ́ méjì-dín-lógún ọdún 1990 jẹ́ òṣèré ará ilẹ̀ amẹ́ríkà àti ọmọ ẹgbẹ́ tí ń lọ síwájú nínú ìgbìmọ̀ ti screen actor's guild ó jẹ́ gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí broadway àti àwọn ipa rẹ̀ bí ìyá nínú àwọn eré ìwòrán lẹ́sẹsẹ tó ní iy...
mercedes ruehl american actress mercedes ruehl ni a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu february ni ọdun 1948 jẹ óṣèrè lobinrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbèsi àyè àràbinrin naa ruehl ni a bisi jackson heights queens new york city fun mercedes j ruehl ólukọ ati vincent ruehl agenti ti fbi babà óṣèrè...
margaret rutherford dame margaret taylor rutherforddbe ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kaarun ọdún 1892 tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kéjììlélógún oṣù karun ọdún 1972 ó jẹ́ òṣèrébinrin to gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo nígbà áye rẹ̀ó dí gbajúgbajà leyin ìjà ogun àgbáyé ẹlẹ́kèejì
eva marie saint american actress born 1924 eva marie saint tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù kẹfà ọdún1924 jẹ́ òṣèrè fíìmù amẹ́ríkà tíátà àti tẹlẹfísọ̀n ní fún ìgbà tó ju ọgọ́jẹ ọdún lọ ó gba àwọ́ọ̀dù akadẹ́mì àti primetime emmy award pẹ̀lú yíyàn fún golden globe award àti british academy film awards lẹ́ẹ̀mejì lẹ́yìn ikú o...
gale sondergaard american actress 18991985 gale sondergaard je óṣèrè lóbinrin ilẹ america ti a bini óṣu febuary ọdun 1899 to si ku ni óṣu august ọdun 1985 igbesi ayè arabinrin naa ósèrè lóbinrin naa ni a bisi ilu litchfield minnesota fun hans sondergaard ati anna kirstine søndergaard sondergaard fẹ́ òṣèré lọ́kùnrin nei...
mira sorvino american actress born 1967american actress born 1967ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ mena suvari mira katherine sorvino wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdílọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1967 jẹ́ òṣèré amẹ́ríkà ó gba àwọ́ọ̀dù akadẹ́mì àti golden globe fún òṣèré tó segi lẹ́yìn ọgbà fún ipa rẹ̀ ní eré woody allen tó pẹ̀ ní mighty aphr...
maureen stapleton lois maureen stapleton jẹ́ òṣèré sinimá ágbéléwò tó gba ámìn ẹ̀yẹ akádẹmì gẹ́gẹ́ bí òṣèrébìnrin aṣègbè fún olú ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ ìbẹ́rẹ́ ayé àti ètò ékọ́ rẹ̀ wọ́n bí stapleton sí troy new yorktí awọn òbí rẹ̀ jẹ́ john p stapleton ati irene née walsh
mary steenburgen mary steenburgen tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹ́jọ ọdún 1953 je òṣérébinrin alawaadaolórin orílẹ̀ èdè america to gba ebun akademi ti obinrin osere keji didarajulo ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rè mary steenburgen ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹ́jọ ọdún 1953 sí newport arkansas si ídíle nellie mae née wall ati mauri...
beatrice straight beatrice whitney straight tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1914 tí ó sìn kú ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 2001 nígbà ayé rẹ̀ jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti gbajúmọ̀ nínú ẹbí whitney ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ academy award àmìn ẹ̀yẹ tony àti adíje àmìn ẹ̀yẹ emmy
tilda swinton british actress tilda swinton je óṣèrè lobinrin ti ilẹ british osere to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbesi ayè arabinrin naa katherine matilda swinton ni a bi ni ọjọ kàrun óṣu november ọdun 1960 si ilu london fun judith balfour 1929-2012 ati sir john swinton 1925-2018 baba óṣère lobi...
marisa tomei marisa tomei tí a bí ní oṣù kejìlá ọjọ́ kẹrin ọdún 1964 jẹ́ òṣèré obìnrin ilẹ̀ amẹ́ríkà ó jẹ́ olùgbà orísirísi iyì lára rẹ̀ ni àmì ẹ̀yẹ akádẹ́mì ní àfikún sí àwọn yíyàn tó gbà fún british academy film award daytime emmy award kan golden globe award méjì àti screen actors guild award mẹ́ta lẹ́hìn iṣẹ́ rẹ̀ l...
claire trevor claire trevor wemlinger tí wọ́n bí ní oṣù kẹ́ta ọjọ́ kẹ́jọ ọdún 1910tí ó sì fi ayé lẹ̀ ní oṣù kẹ́rin ọdún 2000 jẹ́ òsèré amẹ́ríkà ó ṣe àfihàn rẹ̀ nínu fíìmù 65 feature láti ọdún 1933 títí di ọdún 1982 tí ó jẹ́ kí ó gba ààwọ́ọ̀dù academy award for best supporting actress fún ipa rẹ̀ ní key largo 1948 wọ́n ...
miyoshi umeki japanese-american actress and singer miyoshi umeki ti a bini ọjọ kẹjọ óṣu may ni ọdun 1929 je óṣèrè lóbinrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbesi àyè óbinrin naa miyoshi ni a bini otaru hokkaido óṣèrè lobinrin naa jẹ ẹnì to kèrè ju larin awọn ọmọ mẹsan ti baba rẹ bi oludasilẹ ilè iṣ...
jo van fleet american actress 19151996catherine josephine van fleet tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkọ̀ndílọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1915 tí ó sì fi ayé lè ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà ọdún 1996 jẹ́ òṣèrè orí-ìtàgé fíìmù àti tẹlẹfísọ̀n amẹ́ríkà ní gbogbo ìgbà pípẹ́ tó fi ṣe eré níbi ọdún ogójì ó sáábà máa ń kópa ẹni tó ju ọjọ́ orí ẹ̀ lọ ...
rachel weisz english actress born c 1970ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ raquel welch tàbí rachel wyse rachel hannah weisz wọ́n bí ní ọjọ́ kéje oṣù kẹ́ta ọdún 1970 tàbí 1971 ó jẹ́ òsèrè gẹ̀ẹ́sì ó gbà àwọn àwọ́ọ̀dù bíi an àwọ́ọ̀dù akadẹ́mì golden globe award screen actors guild award laurence olivier award critics' choice award ...
dianne wiest dianne evelyn wiest tí a bí ní oṣù kẹta ọjọ́ kejì-dín-lọ́gbọ̀n ọdún 1848 jẹ́ òṣèré ilẹ̀ amẹ́ríkà ó ti gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀rí méjì fún òṣèré àtìlẹ́yìn tí ó dára jùlọ fún ọdún 1986 nínú hannah and her sisters àti ọdún 1994 bullets over broadway méjèjì èyí tí woody allen ṣe ìtọsọ́nà fún ìkan lára rẹ̀ ni golden gl...
shelley winters american actress 19202006 shelley winters august 18 1920 january 14 2006 jẹ óṣere lobinrin to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo igbesi aye arabinrin naa shelley winters jẹ óṣere lobinrin ilẹ amẹrica ti iṣẹ rẹ lọ fun ọdun mẹwa lọnọ meje ti ó si ti yọju ni óriṣiriṣi èrè agbelewoshelley ni ...
teresa wright muriel teresa wright oṣù kẹwàá ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n ọdún 1918 sí oṣù kẹta ọjọ́ kẹfà ọdún 2005 jẹ́ òṣèré america kan wọ́n yàn-án lẹ́ẹ̀mẹ́jì fún akádẹ́mì award fún òṣèré àtìlẹ́yìn obìnrin tó dára jùlọ ní ọdún 1914 fún iṣẹ́ rẹ̀ tó gbé e jáde ní the little foxes àti ní ọdún 1941 fún mrs miniver ní ọdún kan ...
renée zellweger renée kathleen zellweger ọjọ́-ìbí osu kerin ojo kaarundinlogbon 1969 jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀ṣèrébìnri ọmọ amẹ́ríkà tí ó ti gba àmìn-ẹ̀yẹ ebun akademi gẹ́gẹ́ bí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnri tó dára jùlọ wọ́n bíi ní ìlú texas ní zellweger ó sìn kàwé gboyè nínú ìmọ̀ lítíréṣọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì english literature ní univer...
catherine zeta-jones catherine zeta-jones cbe oruko abiso catherine zeta jones 25 september 1969 je osere ara welsi to gba ebun akademi bi obinrin osere keji didarajulo ati ebun tony igbesi aye arabinrin naa abi catherine si swansea arabinrin naa gbero lati jẹ óṣèrè lobinrin lati kekere nibi ti o ti kopa ninu akojọpọ w...
oṣù kẹjọ 27
oṣù kẹrin 23
fabián alarcón fabián alarcón je aare orile-ede ekuador tele
humberto albornoz humberto albornoz je aare orile-ede ekuador tele
eloy alfaro eloy alfaro je aare orile-ede ekuador tele
otto arosemena otto arosemena je aare orile-ede ekuador tele
carlos julio arosemena monroy carlos julio arosemena monroy je aare orile-ede ekuador tele
carlos julio arosemena tola carlos julio arosemena tola je aare orile-ede ekuador tele