raw_text
stringlengths
2
128k
transkei
mvezo mvezo je abule kekere kan ni eba odo mbashe ni agbegbe umtata to je oluilu transkei ibi kan ni apailaorun guusu orile-ede guusu afrika
umtata
mthatha mthatha formerly umtata je ilu kan ni guusu afrika
qunu qunu je is a small rural abule oko kekere kan ni igberiko eastern cape ni orile-ede guusu afrika guusu-iwoorun ilu mthatha
immanuel hermann fichte immanuel hermann von fichte 18 july 1796 8 august 1879 je amoye ara jemani ati omokunrin johann gottlieb fichte ninu imoye re o je asetolorun be sini o lodi gidigidi si imoye ile-eko hegel
thomas kuhn thomas samuel kuhn july 18 1922 june 17 1996 je asefisiksi ati amoye ara amerika to kowe orisirisi nipa itan sayensi
yoon boseon
yun bo-seon orúkọ ará kòréà kan nìyí orúkọ ìdílé ni yun bo-seon korea윤보선 hanja尹潽善 august 26 1897 july 18 1990 je alakitiya ilominira ati oloselu ara korea ati aare ile korea guusu lati 1960 dee 1962
nelson mandela international day
ọjọ́ mandela ọjọ́ mandela èyí jẹ́ ọjọ́ kan tí wọn fi ka fún ẹ̀yẹ síse láti lẹ̀ ṣèrántí ẹni iyì nelson mandela
planeti
syngman rhee syngman rhee tabi yi seungman march 26 1875 july 19 1965 lo je aare orile-ede korea guusu akoko
yi seungman
coat of arms of hungary
frantz fanon frantz fanon july 20 1925 december 6 1961 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè faransé oníwọsàn ààrùn ọpọlọ amoye olujidide àti oǹkọ̀wé tí àwọn ìwé rẹ̀ dá lórí àwọn ẹ̀kọ́ ìgbà eyin imusin critical theory ati marxism
hosea ayoola agbola
amílcar cabral
emblem ilẹ̀ àlgéríà
ẹ́mblẹ́m ilẹ̀ àlgéríà
emblem ilẹ̀ algeria
chang myon orúkọ ará kòréà kan nìyí orúkọ ìdílé ni chang myon korea장면 hanja張勉 august 28 1899 june 4 1966 je alakitiyan ilominira ati oloselu ara korea ati igbakeji aare ile korea guusu lati 1956 dee 1960 ati alákòóso àgbà leemeji 1951-1952 ati 1960 - 1961
tsẹ́kíà
masiela lusha masiela lusha ojoibi october 23 1985 je osere ara amerika
truong tan sang truong tan sang ojoibi january 21 1949 ni adugbo duc hoa igberiko long an french indochina ni aare ile vietnam ile igbimo asofin vietnam diboyan pelu ibo 477 9712 ni july 2011
nguyen minh triet
nguyen tan dung
ìgbìmọ̀ agbógunti ìwàọ̀daràn òkòwó àti ìnáwó economic and financial crimes commission tabi ìgbìmọ̀ agbógunti ìwàọ̀daràn òkòwó àti ìnáwó jẹ́ àjọ agbófinró lorílẹ̀-èdè nàìjíríà tó ń gbógun ti àwọn ìwà ọ̀daràn tó jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ètò-ajé àti ìsúnná-owó
èdè abanyom èdè abanyom
èdè afade èdè afade
èdè ẹdó
èdè lituéníà èdè lituéníà lietuvių kalba
àwọn èdè austronésíà ẹbí àwọn èdè kan nìyí tí èdè tí ó wà nínú rẹ̀ tó ọgọ́fà àwọn tí ó ń sọ àwọn èdè yìí tó àádọ́rin lé ní igba mílíọ̀nù 270 million wọ́n ń sọ wọ́n láti madagascar dé eastern island wọ́n tún ń sọ wọ́n láti taiwan dé hawal títí dé new zealand wọ́n tún máa ń pe austronesian yìí ní malayo-polynesian ó jẹ́ ...
àwọn èdè adámáwá-ubangi àwọn èdè adamawa-ubangi àkójopò àwon ède kan ni yí tí wón tó márùn-ún-dín-lógósàn-án 175 wón wà ní apá àríwá ààrin gbùngbùn aáfíríkà lati apá ìlà oòrùn nàìjíríà títí dé ìwò oòrùn sùdáànù omo egbé náíjá kongò niger-congo ni wón wón n pè wón ni ìla-oòrun adamawá adamawa-eastern télè díè lára àwon ...
àwọn èdè adamaua-ubangi
ìgbéríko àrin kẹ́nyà ìgbéríko àrin kenya ni agbegbe 'keta to o kere ju lo ni orile ede kenya lehin agbegbe nairobi ati agbegbe iwo oorun pelu àpapọ̀ iye ààlà 13191 km2 50931 sq magegbe naa wa ni iha ariwa si ilu nairobi ati iha iwo o'orun si oke kenya ni ikaniyan to odun 2009 agbegbe naa ni iye eniyan olùgbé 4383743 ol...
agbegbe aarin
central province kenya
egbé ọmọ odùduwà egbe omo oduduwa ni oruko egbe ti obafemi awolowo pelu awon alagba pataki ni ile yoruba da sile ni odun 1945 ni ilu londonu
okun india
gusu sudan
yoshihiko noda yoshihiko noda 野田 佳彦 noda yoshihiko born 20 may 1957 je oloselu ara japan ti egbe demokratiki ile japan dpj omo egbe ile awon asoju ninu diet ile asofin lati 2 september 2011 o di alakoso agba ile japan leyin ti akihito oba ile japan yansipo
tony tan keng yam orúkọ ará ṣáínà kan nìyí orúkọ ìdílé ni tan tony tan keng yam ojoibi 7 february 1940 ni singapore ni aare ile singapore keje lowolowo
lech walesa
zhengzhou èyí jẹ́ agbègbè kàn ní orílé èdè china ni zhengzhou tí wọn fisílẹ̀ láti máa ṣe káràkátà àwọn ọjà
oṣù kẹ̀wá 5
lady gaga lady gaga oruko ibi stefani joanne angelina germanotta ojo ibi 28 march 1986 je olorin/akorin omo ile amerika jelena rozga
kroatia
539 sk ọ̀rúndún 70k sk | ọ̀rúndún 60k sk | |► 539 sk | | ► | ọdún 539 sk síwájú krístì
539 bc
walter brattain
lê ðức thọ
ìròyìn oṣù kẹ̀wá 2011
nobel fún ìwòsàn
nobel fún àlàfíà
nobel fún litiréṣọ̀
nobel fún kẹ́místrì
nobel fún físíksì
leymah gbowee leymah roberta gbowee bíi ọjọ́ kínín oṣù kejí ọdún 1972 jẹ́ alákitiyan fún àláfíà ọmọ orílẹ̀ èdè liberia tó ṣètò̀ ìrìnkankan àláfíà tó fi òpin sí si ogun abẹ́lé orílẹ̀ èdè liberia kejì ni ọdún 2003
tawakel karman tawakel karman lárúbáwá ‎ tawakkul karmān tawakul tawakkul je oloselu ara yemen to je omo egbe al-islah ati alakitiyan awon eto omoniyan to tun je olori egbe women journalists without chains to dasile ni 2005
tomas tranströmer tomas gösta tranströmer bíi ní ọjọ́ karùndínlógun oṣù kẹrin ọdún 1931 jẹ́ olùkọ̀wé akoewì àti ayédèdà ará sweden tó jẹ́ pé àwọn ewì tó kọ ti jẹ́ yiyilededa sí èdè tó jú ọgọ́ta lo
dan shechtman dan shechtman hebrew דן שכטמן ojoibi january 24 1941 in tel aviv je asesayensi ara israel to gba ebun nobel
saul perlmutter saul perlmutter born 1959 je asefisiksi-irawo ara amerika to unsise ni lawrence berkeley national laboratory ati ojogbon fisiksi ni university of california berkeley
adam riess adam guy riess ojoibi december 1969 washington dc je asefisiksi-irawo ara amerika ni johns hopkins university ati ni space telescope science institute to gbajumo fun iwadi re fun lilo supernovae bi cosmological probes
adam g riess
adam guy riess
brian p schmidt
brian schmidt brian p schmidt born february 24 1967 is a distinguished professor australian research council laureate fellow and astrophysicist at the australian national university mount stromlo observatory and research school of astronomy and astrophysics and is widely known for his research in using supernovae as co...
bruce beutler bruce alan beutler ojoibi december 29 1957 je aseoroajesara ati aseiseabinimo ara amerika lapapo pelu jules a hoffmann won gba abo kan ebun nobel 2011 fun iwosan fun iwari won nipa imusise ajesara inu ara abo keji lo si ralph m steinman fun iwari re lori ahamo dendritiki ati ipa re ninu ajesara alamuye
jules a hoffmann jules a hoffmann ojoibi 2 august 1941 je omo luksembourgish ara fransi aseoroigbe
jules hoffmann
ralph m steinman ralph marvin steinman january 14 1943 september 30 2011 je was a canadian aseoroajesara ati aseoroigbe ahamo ara kanada ni rockefeller university to da oro to unje ahamo dendriti ni 1973
apple
apple inc apple inc tí wọn ń pè ní apple computer inc jẹ́ ilé-iṣẹ́ kàn tí ó wà káàkiri àgbáyé tí ó gúnwà sí orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà tí ó ṣètò ṣíṣẹ̀dá àti títa èròjà kọ̀m̀pútà àwọn èròjà atọ̀nà alànà kọ̀m̀pútà àti àwọn kọ̀m̀pútà àdálò
deer
àgbọ̀rín àgbọ̀rín tàbí àgbọ̀nrín je awon eranko afọmúbọ́mọ abilenuje ni inu ebi cervidae
mya harrison
mýa mýa marie harrison ojoibi october 10 1979 to gbajummo bi mýa je akorin atokun awo-orin ati osere ara amerika
beyoncé knowles beyoncé giselle knowles bíi ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsán odún 1981 tí wọ́n mọ̀ sí beyoncé jẹ́ alágbe tí ó ń kọ rb àti ẹlẹ́ṣọ́ aṣọ ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà wọ́n bíi ní houston ní texas níbi tó ti lọ sí ilé ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ọnà síṣe knowles kọ́kọ́ gbajúmọ̀ ní òpin èwádún 1990 gẹ́gẹ́ bí asíwájú akọrin ẹgbẹ́ olórin rb des...
beyoncé
beyonce
mya
nicanor duarte frutos
chuck berry charles edward anderson chuck berry ojoibi october 18 1926 - 18 march 2017 je alugita akorin ati oluko-orin ara amerika ati ikan larin awon alewaju ninu orin rock and roll
diana ross diana ernestine earle ross born march 26 1944 je olorin ati osere ara amerika ross loje olorin asiwaju fun egbe akorin the supremes ni motown nigba ewadun 1960 leyin to fi egbe yi sile ni 1970 ross bere si ni dakorin be sini o bere si ni se filmu ati ere ni broadway o gba idaloruko fun ebun akademi bi osere ...
wilt chamberlain wilton norman wilt chamberlain august 21 1936 october 12 1999 je ara amerika to gba boolu-alapere ni nba fun philadelphia/san francisco warriors philadelphia 76ers ati los angeles lakers bakanna o tun gba boolu fun harlem globetrotters ko to dipe o lo si nba
art tatum arthur art tatum jr october 13 1909 november 5 1956 je onipiano jazz ati virtuoso ara amerika to mo ilu orin lu daada bo ti le je pe o fo loju
thomas j sargent thomas john tom sargent ojoibi july 19 1943 je aseitookowo ara amerika to gba ebun nobel iwadi re je lori isiseitookowogbangba isiseitookowo owo ati asiko eleseese isuwon-itookowo
ọ̀rọ̀ayéijọ́un ọ̀rọ̀ayéijọ́un archaeology tabi archeology lede geesi lati ede griiki archaiologia arkhaios ayeijoun and -logia -logy je agbeka awujo omoniyan lakoko nipa iwari ati ituyewo asa ohun-ini ati awon data ayika ti won fi seyin ti ninu won je iseowo onaikole onidajuayika ati ojuile asa eyun akoole oloroayeijou...
archaeology
archeology
norwegian language
èdè ará nọ́rwèy èdè ará nọ́rwèy norsk je ede north germanic kan ti won un so lagaga ni norway nibi to ti je ede onibise
octave mirbeau octave mirbeau february 16 1848 in trévières calvados - february 16 1917 je ara fransi oniroyin alagbewo iseona olukowe irinajo oniweroyin onitan-enu ati akoere oriitage ninu awon iwe re niwonyi le calvaire 1886 l'abbé jules 1888 sébastien roch 1890 le jardin des supplices 1899 le journal d'une femme de ...
alexander crummell alexander crummell march 3 1819 new york city - september 10 1898 red bank new jersey je alufa ojogbon ati asetolomoorile-ede ara african
booker t washington booker taliaferro washington april 5 1856 november 14 1915 je oluko olukowe afenuso ati olori oloselu ara amerika ohun ni o eni asiwaju lawujo awon omo afrika amerika ni amerika lati 1890 de 1915 bi asoju togbeyin ninu awon iran olori alawodudu amerika ti won bi sinu oko-eru o gbenuso fun ogunlogo a...
oṣù kẹrin 5
virginia us state
oṣù kọkànlá 14
booker taliaferro washington