raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
garcinia magnifolia species of plant garcinia magnifolia tí a tún mo sì bebasajo tàbí giant leaf madrono ni igi olódodo ninu ebi reclusiaceae guttiferaeepipeth to se koko magnifolia wá láti oro latin magni = po ga àti folia = ewe ati to je mo igi èwe tó já púpò |
annona squamosae species of tree annona squamosa jẹ́ igi kékeré tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka láti ara ẹ̀yà annonaceae tó ń so èso tó ṣe é jẹ tí wọ́n ń pè ní sugar apples tàbí sweetsops ó ní ìfẹ́ sí tropical lowland climate ju àwọn ìyókù rẹ̀annona reticulata àti annona cherimola èyí tí èso wọn sábà máa ń ní orúkọ kan náà èyí t... |
loquat species of plantojúewé yìí jẹ mọ́ nípa a species of flowering plants called japanese medlar fún other uses ẹ wo medlar fún the band ẹ wo loquat band loquat eriobotrya japonicatí à ń pè ní biwa ní japan jẹ́ igi èso kékeré tàbí ńlá tí à ń gbín nítorí èso-ọsàn rẹ̀ fún orọ̀-ajé àti fún ewé e rẹ̀ èyí tí a fi ń ki àgb... |
ficus carica igi ọpótò je eka gbóògì eso ti ficus carica omo igi kékeré ni ogbin ododo nínú ìdílé moraceae native sí mediterraneanibugbe papọ pẹlu awọn western and southern asia won ti ko ebe lati igba ìwásè ọ sí ti dàgbà gidigidi ni gbogbo orilẹ ede ayé ficus carica o je ọkan ninu of the genus ficus tí o kun fun ẹgbẹr... |
honey dew melon honeydew melon jẹ́ ọ̀kan lára méjì nínú gbòógì oríṣi èso tí a yàn gbìn ní ọ̀wọ́ èso cucumis melo inodorus àbùdà a rẹ̀ jẹ́ èyí tí ó nípọn tí ó dán tí kò sí ní òórùn dídùn èyí tó jé èkejì nínú ọ̀wọ́ yìí ni wrinkle-rind casaba melon àbùdá honey dew ní àbùdá roboto ó sì gùn ní ìwọn mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n sí mejìlé... |
haruka citrus haruka citrus tamurana x natsudaidai jẹ́ citrus cultivar tó dàgbà ní japan àti korean peninsula orísun haruka ti kọ́kọ́ ṣe àwárí ní ehime prefecture japan ní kété tí a ti rò pé ó jẹ́ ìyípadà adáyébá ti hyuganatsu citrus tamurana o ti wa ni bayi pe o jẹ arabara laarin hyuganatsu ati natsudaidai citrus nats... |
diospyros blancoi diospyros blancoi synonym diospyros discolor tí a mọ̀ sí velvet apple velvet persimmon kamagong tàbí mabolo tree jẹ́ igi ti àwọn genus diospyros of ebony trees àti persimmons ó máa ń so èso tó da with a fine velvety reddish-brown fur-like covering the fruit has a soft creamy pink flesh with a taste an... |
denise mobolaji ayaji-williams denise mobalaji ajayi-williams ni aṣàkóso àti olùdásílẹ̀ silicon valley- nigerian economic development inc sv-ned sv-ned inc jẹ́ ìtàkùn tó so silicon valley àti gbogbo ayé pọ̀ ní ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn sv-ned inc ti ní tó ènìyàn 1 billion tí wọ́n sì ti ní ìbáṣepọ̀ tó dánmọ́rán pẹ̀lú àwọn oníṣ... |
tomi adeyemi tomi adeyemi tí wọ́n bí ní august 1 1993 jẹ́ ònkọ̀wé àti olùkọ́ àkọsílẹ̀ àtinúdá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ilẹ̀ america ó gbajúmọ̀ fún ìwé ìtàn-àròsọ rẹ̀ children of blood and bone èyí tó jẹ́ àkọ́kọ́ nínú ìtàn legacy of orïsha trilogy tí henry holt books for young readers ṣá̀tẹ̀jáde rẹ̀ ìwé yìí gb... |
bim adewunmi bim adewunmi jẹ́ akọ̀ròyìn ilẹ̀ britain òun ni aṣagbátẹrù this american life ó sì ti fìgbà kan ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí òǹkọ̀wé ní buzzfeed àti the guardian ó ṣe olóòtú ètò thirst aid kit pẹ̀lú òǹkọ̀wé nichole perkins láti ọdún 2017 wọ ọdún 2020 eré rẹ̀ àkọ́kọ́ ni hoard tí wọ́n ṣàfihàn ní tíátà arcola theatre ní oṣ... |
yemi adesanya yemi adesanya jẹ́ òǹkọ̀wé oníṣirò-owó ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀ the arts civics table tact ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ ni musings of a tangled tongue ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ orúkọ àbísọ rẹ̀ ni jolaoyemi doyinsola olatubosun wọ́n sì bi sínú ìdílé elénìyàn mẹ́jọ ó lọ ilé-ìwé ní ìbàdàn ní ìpí... |
emma dabiri emma dabiri frsl tí wọ́n bí ní 25 march 1979 jẹ́ òǹkọ̀wé onímọ̀ àti akàròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè ireland ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ ni àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ don't touch my hair ni ó tẹ̀ jáde ní ọdún 2019 wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ẹgbẹ́ he royal society of literature ní ọdún 2023 ìgbésí ayé rẹ̀ ìlú dublin ni wọ́n bí dabiri sí ìy... |
ekunrawo 'adeleke timileyin tunde ti a mọ̀ siekunrawo jẹ akọrin ati awoṣe afrobeat ti russia-nigeria igbesi aye ibẹrẹ ati iṣẹ orile-ede naijiria ni won bi tunde sugbon o lo si orile-ede russia lati tesiwaju ninu eko re volgograd state university of architecture and civil engineering níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè gẹ́gẹ́ b... |
samson bakare samson bakare jẹ́ oníṣẹ́- ọnà ài ayàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ẹni tí a mọ̀ sí àfihàn rẹ̀ ti àwọn ara dúdú tí ó ní ìpìlẹ̀ òdòdó ó ṣètò àwọn kókó-ọrọ̀ semi-figurative rẹ̀ ní àwọn àwọ̀ dídán ṣíṣe àlàyé ẹwà náà iṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ ìjúwe nípasẹ̀ àwọn ojú tí ń jáde àlàyé pàtàkì lórí iris ati pupil ọmọ ile-iwe baka... |
nicholas hoult nicholas hoult oruko abiso nicholas caradoc hoult oṣù kejìlá 7 1964 je osere ara ilegeesi |
simi bedford simi bedford jẹ́ òǹkọ̀we láti orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó tẹ̀dó sí ìlu britain ìwe rẹ̀ akọ́kọ́ yoruba dancing girl jẹ́ ìtan ìgbésí-ayé-ara-ẹni nípa ọ̀dọ́mọbìrin nàìjíría kan ti wọ́n rán lọ sí orílẹ̀-ède england láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ ni ilé-ẹ̀kọ́ àdáni wọ́n ṣe àyẹ̀wo ìwé náà ní ibi ìtẹ̀wé tí ó sì di kókó ìsọníṣókí... |
helen oyeyemi helen oyeyemi frsl tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejìlá ọdún 1984 jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ ọba àti oǹkọ ìtàn kéékèèké ìgbésí ayé oyeyemi ni a bí ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí a sì tọ́ ní lewisham south london láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin oyeyemi kọ ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ ìyẹn the icarus girl nígbà tí ó ń kàwé fún a-l... |
oluwakemi adejoro ojo oluwakemi adejoro ojo tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí kemi korede jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ aṣagbátẹrù ayẹyẹ wọ́n máa ń ṣàfihàn rẹ̀ nínú àwọn fíìmù yorùbá oluwakemi àti toyin alausa ni wọ́n jọ tẹwọ́bọ̀wé fún honeyglow skin care ní ọdún 2021 ẹni tó ni ilé-iṣé náà ló ṣ... |
maureen ihua maureen ihua jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ nàìjíríà tó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bíi domitila unplanned and unpredictable ó ṣe fíìmù pẹ̀lú liz benson àti regina askia ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ìpínlẹ̀ rivers ni ihua ti wá ó sì lọ sí ilé-ìwé girama ti mariam girls iṣẹ́ tó yàn láàyò ó ti ṣe ìfihàn nínú ... |
domitila 1996 domitilla jẹ́ fíìmù ọdún 1996 ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó ní àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bí i anne njemanze sandra achums ada ameh àti kate henshaw fíìmù náà dá lórí arábìrin kan tó ń tiraka láti rí jíjẹ-mímu nípa ṣíṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó ní èkó apá kejì fíìmù náà ìyẹn domitilla 2 jáde ní ọdún 1999 àtúnṣe rẹ̀ sì máa jáde n... |
the governor fíìmù ilẹ̀ nàìjíríà gomina jẹ́ fíìmù nàìjíríà ti ọdún 2016 tó dá lórí ìlú savannah èyí tí wọ́n ṣe ní ìlú calaba àti cross river ó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́-ìṣẹ̀lú alápá mẹ́tàlá èyí tí olùdarí rẹ̀ jẹ́ ema edosio tí òǹkọ̀tàn sì jẹ́ yinka ogun tunde babalola àti debo oluwatuminu mo abudu ló sì gbé e jáde ìṣàfihàn ìṣàf... |
mama insurance mama insurance jẹ́ fíìmù nàìjíríà ti ọdún 2012 tó dá lórí onílé lan tó kanra mọ́ àwọn ayálégbé rẹ̀ victoria island ni wọ́n ti ya fíìmù yìí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ tí liz da-silva sì gbé é jáde ìsọníṣókí fíìmù náà dá lórí obìnrin onílé kan tó máa ń kanra púpọ̀ tí àwọn ayálégbé rẹ̀ sì jẹ́ àwọn obìnrin tó ń ṣe o... |
lucifer fíìmù nàìjíríà 2019 lucifer jẹ́ fíìmù nàìjíríà ti ọdún 2019 tó dá lórí arákùnrin kan tí gbogbo ènìyàn bẹ̀rù ní agbègbè rẹ̀ tope adebayo àti ibrahim yekini ni olùdarí eré yìí orúkọ ìnagije ibrahim yekini ni itele òun sì ló gbé erẹ́ náa jáde àmì-ẹ̀yẹ ibrahim yekini gba àmì-èyẹ òṣèrékùnrin yorùbá tó dára jù lọ ní ... |
temitope solaja temitope solaja jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ nàìjíríà òǹkọ̀tàn àti aṣagbátẹrù fíìmù ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ temitope solaja jẹ́ ọmọ àkọ́bi àwọn òbí rẹ̀ ìlú sagamu ní ìpínlẹ̀ ògùn ló sì ti wá ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè bachelor's degree nínú ìmọ̀ mass communication láti tai solarin university of education iṣẹ́... |
sunkanmi omobolanle sunkanmi omobolanle jẹ́ òṣèrékùnrin ilẹ̀ nàìjíríà àti olùdarí fíìmù ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn láàyò ọjọ́ kìíní oṣụ̀ kẹta ọdún 1981 ni wọ́n bí i ìlú ilora ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ni ó ti wá òun ni ọmọ gbajúgbajà òṣèrékùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ sunday omobolanle tí gbogb... |
77 bullets 77 bullet jẹ́ fíimù ilẹ̀ nàìjíríà ti ọdún 2019 tí mercy aigbe gbé jáde tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ adebayo tijani ó jẹ́ fíìmù ajẹ́mọ́-ìṣẹ̀lè-tó -le tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ gbajúmọ̀ òṣèré bí itemitope solaja ibrahim yekini àti eniola ajao kópa nínú rẹ̀ ìsọníṣókí fíìmù náà sọ ìtàn ọlọ́ṣà kan tí kò láàánú tó sì ní ìhámọ́ra oòg... |
egg of life fíìmù nàìjíríà ti ọdún 2003 egg of life jẹ́ fíìmù ilẹ̀ nàìjíríà ti ọdún 2003 tó dá lórí ṣíṣe ìwòsàn fún ọmọ-ọba kan tó wà lójú ikú olùdarí fíìmù yìí ni andy amenechi kabat esosa egbon àti ojiofor sì ló kọ ọ́ ìsọníṣókí ọmọ-ọba kan ló wà ní ojú ikú tó sì níló ẹyin àràmàǹdà tó ń mú ìyè wá ó sì níló kí ọ̀wọ́ àw... |
president kuti president kuti jẹ́ fíìmù ilẹ̀ naijiria tí ibrahim yekini gbé jáde azeazat sorunmu ló kọ ọ́ olùdarí fíìmù náà sì jẹ́ tope adebayo àti ibrahim yekini wọ́n ṣàgbéjáde president kuti ní 14 july 2021 ìsọniṣókí president kuti ni alákòóso àwọn ọmọ-ìta tí gbogbo ènìyàn bọ̀wọ̀ fún tí wọ́n sì bẹ̀rù ó dojú kọ ìkọlù ... |
kesari fíìmù 2018 kesari jẹ́ fíìmù yorùbá ti nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2018 èyí tí ibrahim yekini gbé jáde tope adebayo sì ni olùdarí fíìmù yìí ìṣàgbéjáde nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nùwo kan ibrahim yekini tó jẹ́ òǹkọlwé àti olùgbéjáde sọ ọ́ di mímọ̀ pé fíìmù black panther tí òun wò ló fún òun ní ìwúrí láti kọ fíìmù yìí ìsọníṣó... |
rose moss rose rappoport moss tí wọ́n bí ní 1937 jẹ́ òǹkọ̀wé ti orílẹ̀ èdè america tí wọ́n bí ní south africa ó kó lọ sí ìlú america ní ọdún 1961 ó ti ṣe àgbéjáde ìwé ìtàn-àròsọ ìtàn kékèèké ọ̀rọ̀-fún orin àti àwọn ìtàn-àìròtẹ́lẹ̀ ní àfikún ó fìgbà kan jẹ́ olùkọ́ ní wellesley college òun àti barney simon pẹ̀lú rose zwi... |
barney simon barney simon ọjó kẹtàlá oṣù ìgbé ọdún 1932 si ọgbọn ọjó oṣù okundu ọdún 1995 kí a má ṣe dà á pọ mọ́ jacaranda fm radio dj barney simon barney simon jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ south african àti olùdarí fíìmù ìlú johannesburg ní south africa ni wọ́n bi sí ibẹ̀ sì ni ó kú sí ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ simon ṣe àwárí ìfẹ́ rè... |
ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede soviet union ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede soviet union rọ́síà sbórnaya sssr po futbólu сбо́рная ссср по футбо́лу sbórnaya sssr po futbólú je egbe agbaboolu orile-ede ti soviet union lati 1922-1992 lẹhin pipin ti union ẹgbẹ naa ti yipada si ẹgbẹ bọọlu ti orilẹ-ede cis fifa ṣe akiyesi ẹgbẹ agbabọọlu ... |
cat hellisen cat hellisen 31 may 1977 jẹ́ òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè south african tó kọ ìwé ìtàn-àròsọ when the sea is rising red house of sand and secrets àti beastkeeper ìgbésíayé rẹ̀ wọ́n bí cat hellisen sí cape town ó sì ti gbé ní cape town àti johannesburg south africa àti nottingham england lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ìlú sco... |
rozena maart rozena maart tí wọ́n bí ní ọdún 1962 jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ south africa àti ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń gbé ní ìlú durban lọ́wọ́lọ́wọ́ òun ni olùṣàkóso fún centre for critical research on race and identity ó gbajúmọ̀ fún ìwé kíkọ rẹ̀ àti àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹlẹ́yàmẹyà àti ìwà-ipá sí àwọn obìnrin ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i olùkọ... |
anna m louw anna m louw a bí ni ọjọ́ kọkanlelọgbọn oṣu ọpẹ́ ọdun 1913 sí ọjó kejìlá oṣù okundu ọdún 2003 o jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ south africa ìlú calvinia ni wọ́n bi sí bàbá rẹ̀ jẹ́ àgbẹ̀ tó máa ń sin àgùntàn lẹ́bàá ọ̀nà calvinia ní orí oko soetwater ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ kan lórí ọkọ náà o wà ní ìbátan pẹ̀lú à... |
freda linde freda linde 12 december 1915 7 march 2013 jẹ́ òǹkọ̀wé ìwé àwọn ọmọdé àti ògbufọ̀ ti ilẹ̀ south africa èdè afrikaans ló máa ń lò fún ìwé kíkọ rẹ̀ ó ti ṣe ògbufọ̀ àwọn ìwé ọmọdé tó ju àádọ́jọ lọ sí èdè afrikaans french àti german ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti cp hoogenhout award ní ọdún 1964 ayé rẹ̀ ìlú swellendam ni wọ́... |
ijakumo ijakumo the born again stripper jẹ́ fíìmù ajẹmọ́-ìṣiyèméjì ti ọdún 2022 èyí tí toyin abraham gbé jáde tó sì di àgbéléwò ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejìlá ọdún 2022 àwọn tó kópa nínú eré náà ni toyin abraham kunle remi lolade okusanya bimbo akintola olumide oworu lillian afegbai àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kehinde joseph ni... |
lilian afegbai lilian afegbai tí wọ́n bí ní 11 november 1991 jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ nàìjíríà àti aṣàgbéjáde fíìmù agbéléwò ó fìgbà kan jẹ́ akópa nínú ètò big brother africa ní ọdún 2018 ó gba àmì-ẹ̀yẹ africa magic viewers' choice awards amvca fún fíìmù ìbílẹ̀ tó dára jù ní ọdún 2018 ní ọdún 2019 ó ṣe ìdásílẹ̀ ìdókòwò rẹ̀... |
sullubawa awon sullubawa tabi sisulbe jẹ ẹya fulani ti o ni ifihan pataki ni itan ninu jihad ti usman dan fodio ti o da ẹlẹda sokoto awon ile-ọba o jẹ olori ti emirate kano ati emirate katsina bakanna bi emirate ringim ati emirate karaye jẹ ti abi ati kaadi miiran laarin awọn ile-ọbi mẹrin ti emirate zazzau a tún rí wọ... |
sulluba awon sulluba tabi sisulbe jẹ ẹya fulani ti o ni ifihan pataki ni itan ninu jihad ti usman dan fodio ti o da ẹlẹda sokoto awon ile-ọba o jẹ olori ti emirate kano ati emirate katsina bakanna bi emirate ringim ati emirate karaye jẹ ti abi ati kaadi miiran laarin awọn ile-ọbi mẹrin ti emirate zazzau a tún rí wọn ní... |
road to yesterday film road to yesterday jẹ́ fíìmù ajẹ́mọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2015 èyí tí ishaya bako darí lára àwọn akópa inú fíìmù náà ni genevieve nnaji àti oris erhuero tí wọ́n jẹ́ olú ẹ̀dá-ìtàn àti majid michel pẹ̀lú chioma 'chigul' omeruah tí wọ́n ṣe ẹ̀dá-ìtàn mìíràn fíìmù náà tí geneviev... |
anny robert nigerian celebrity photographer born 1990 anietie “anny robert tí wọ́n bí ní ọjọ́ méjìdínlọ́gbọ̀n oṣùn kẹ̀jọ ọdún 1990 jẹ́ ayàwòrán ní oríẹ̀-ẹ̀dẹ̀ è nàìjíríà àti creative director ní ìpínlè niger nàìjíría robert kọ́ ẹ̀kó nípa computer science ní iléẹ̀kọ́ gíga convenant robert started his career in graphic a... |
ade adekola nigerian artist b 1966ade adekola tí a bíi ni ọdún 1966 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti onímọ̀ nípa oríṣiríṣi ẹ̀kọ́ àwọn ènìyàn mọ̀ọ́ ṣí oníṣẹ́-ọnà ayàwòrán olúyàwòran oníṣẹ́-ọ̀nà ìgbàlódé àti ọ̀ǹkọ̀wé ó ń gbé ní ìlú èkó wọ́n bí ade adekola ni oṣù kẹ̀ta march ọjọ́ kẹ̀ta 1966 ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó l9 sílé... |
olu ajayi olu ajayi ti a bi 18 august 1963 jẹ́ olórin alamọdaju ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà onise ọ̀nà alaworan ati oluyẹwo aworan pẹ̀lú ìrírí ogójì ọdún ní adaṣe ilé ìṣeré àti ìṣàkóso iṣẹ́ ó jẹ́ alága ti o ti kọjá tí society of nigerian artists lagos state chapter ati pe o jẹ olutọju ti guild of professional artists of ni... |
yinka edward nigerian cinematographeryinka edward tí a bí ní jos nigeria jẹ́ ayàwòrán sinimacinematographer nílẹ̀ nàìjíríà ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ fíìmù rẹ̀ oc tober 1 93 days a love story winner of bafta's best british short animation category 2017 confusion na wa and lionheart career in the early years of his career afte... |
alimi adewale alimi adewale tí a bí ní may 8 1974ó jẹ olóṣèré wíwò àti olùyàwòrán ní àwùjọ àwọn ènìyàn ní orílẹ èdè naijiria ṣùgbọ́n ìfẹ́ rẹ̀ sí iṣẹ́ ọnà àti àwọn ìfihàn ṣe ìwúrí ìfẹ́ rẹ̀ láti di òlóṣèré àwọn iṣẹ́ rẹ̀ máa ń sábà dálé àárín ìlú ìṣàwárí rẹ̀ pèlú gbogbo ìgbekalẹ̀ rẹ̀ tí àwọn ará ìlú ojoojúmọ́ àti àwọn kók... |
chris ofili christopher ofili a bí i ní ọjọ́ kẹwàá oṣù ọ̀wàwà ọdún 1968 ó jẹ́ ayàwòrán ilẹ̀ britain tí ó gbajúmọ̀ fún àwọn iṣẹ́ ẹ rẹ̀ tó máa ń ní ìgbẹ́ erin nínú ó gba àmì-ẹ̀yẹ turner prize ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwon ọ̀dọ́ tó jẹ́ ayàwòrán ní ilẹ̀ britain láti ọdún 2005 ni ofili ti ńṣiṣẹ́ ní trinidad and tobago níbi tí ó ... |
tayo adenaike tayo adenaike ó jẹ́ ẹni tí a bí ní ọdún 1954 arákùnrin yìí sì jẹ́ oluyaworan ní orílẹ̀ èdè omo nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ̀ ọmọ bíbí ìlú idanre ní adenaike jẹ́ ní ẹ̀yà yoruba parentage ni ọdún 1967 ó kọ́kọ́ ṣe àfihàn sí bí ó ṣe ń kẹ́kọ̀ọ́ d déédéé lórí iṣẹ ọnà ni ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ni warri... |
emamode edosio emamode edosio tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ema jẹ́ òṣèré fíìmù àti olùdarí fíìmù ọmọ orílẹ-èdè nàìjíríà ó gba òye bsc ní computer science láti ogun state university ó kọ ẹ̀kọ́ ṣíṣe fíìmù oní-nọ́mbà ní new york film academy nyfa àti motion pictures ni motion pictures institute ti michigan amẹ́ríkà ó gba fíìmù... |
uche okeke christopher uchefuna okeke tí wọ́n bí ní ojó ogbòn ni odún 1933 tó sì kú ní ojo karùn osù kinni sere odún 2016 tí ó sì tún ń jẹ́ uche okeke jẹ́ ayàwòrán agbẹ́gilére àti olùkọ́ ó jẹ́ olùkọ́ oníṣẹ́-ọnà ní nàìjíríà ìpìlẹ̀ wọ́n bí christopher uchefuna okeke ní ojó ogbòn osu kerin igbe ni odun1933 ní ìlú nimo nji... |
ikechukwu francis okoronkwo ikechukwu francis okoronkwo tí wọ́n bí ní 27 may 1970 jẹ́ ayàwòrán agbẹ́gilére àti òǹkọ̀wé ti ilẹ̀ nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ikechukwu ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù ẹ̀bìbì ọdún 1970 sínú ìdílé francis okoronkwo ní oguta nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ifáfitì ti port-harco... |
kolopin la bùárí ọlálékan olúwaṣẹ́gun ti a bí ní oṣù kẹ́rìn-ín oṣù igbe april ni ọdún 1987 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ s unlimited la jẹdàŕ music video director ti nàìjíríà ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oríṣi orin àti àwọn òṣèré pẹlú olamide phyno timaya àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn mìíràn ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ a bí buari olalekan olu... |
unlimited la buari olalekan oluwasegun ti a bíi ní oṣù kẹ́rìn-ín april ni ọdún 1987 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí unlimited la jẹ́ music video director ti nàìjíríà ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oríṣi orin àti àwọn òṣèré pẹlú olamide phyno timaya àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn mìíràn ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ a bí buari olalekan oluwasegun ... |
ayo akinwande àyo akínwándé wón bíi ni ìlú èkó ni orile-ede nàìjíríà ó jé olórin ìran ìgbàlódé ọmọ nàìjíríà olùdarí àti òǹkọ̀wé ó jẹ́ olókìkí fún àwọn iyàwòran multimedia tí ó hàn gbangba àti ṣiṣẹ́ lórí ìwé ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ ayo akínwándé tí wọ́n bí sí ìlú èkó  ní orílè èdè nàìjíríà ó kọ ẹ̀kọ́ nípa áti a y... |
ebele okoye ebele okoye tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí omenka ulonka jẹ́ olùṣàgbéjáde fọ́nrán oníṣẹ́-ọnà àti ayàwòrán ọmọ nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú berlin wọ́n bi ní ojo kefaosu owara odun 1969 ní ilu onitsha ni ipinle anambra ní orile ede nàìjíríà wọ́n mọ̀o gẹ́gẹ́ bí i asajubinrin adulawo onimo nipa ise ona ayaworan ó ni ìrì... |
asiru olatunde asiru olatunde 19181993 jẹ́ ayàwòrán alágbẹ̀dẹ ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jé ọkan lára àwọn gbajúgbajà ayàwòrán ní ìlú òṣogbo ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ayàwòrán kékeré kan tí wọ́n darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́-ọnà kan ìyẹn oshogbo school of art àwọn àwòrán rẹ̀ dá lórí àwọn ìtàn ìgbaani ti ilẹ̀ yorùbá àti àw... |
mike omoighe a bí michael akhaine osebhajimete omoighe tí ìnagijẹ sì ń jẹ́ mike omoighe ní ọjọ́ kọọkànlá oṣù keje agẹmọ ọdún 1958 ó sì jáde láyé ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kìn-ín-ní ṣẹrẹ ọdún 2021 ó jẹ oníṣẹ́ ọnà aláfọwọ́gbékalẹ̀ àti olùkọ́ iṣẹ́ ọnà aláfọwọ́gbékalẹ̀ a bí mike ni ìlú opoji ekpoma ní ìpínlẹ̀ ẹdó ó dàgbà sí ... |
nengi omuku nengi omuku tí wọ́n bí ní ọdún 1987 jẹ́ ayàwòrán agbẹ́gilére àti oníṣẹ́-ọnà ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí i ní ìlú asaba ìpínlẹ̀ delta ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà omuku kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ba àti ma ní slade school of fine art university college london àwọn àmì-ẹ̀yẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣé ne... |
anne landsman anne landsman ti a bi ni ọjọ́ kerinla osu kerin odun 1959 jẹ́ òǹkọ̀wé wọ́n bíi ni worcester south africa ó jẹ́ ọmọ dọ́kítà ó sì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́-gboye ni university of cape town ati columbia university o sise oluko títì di ọdún 2001 o tun tesiwaju ninu ise olùkọ́ ní ile-eko the new school university ni new y... |
lauren liebenberg ìpìlẹ̀ wọ́n bí liebenberg ni rhodesia sugbon gegebi omode láti kékeré ni ó ti fi ilu zimbabwe silẹ lọ sí ilẹ olòmìnira ti south africa eléyìí tí wọ́n jọ pín ààlà ó lọ sí brescia house èyi tí ó jẹ́ ilé-eko ijo aguda fún àwọn obìrin ni johannesburg lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́-gboyè kín-ní ní university of sout... |
lauren liebenberg |
òndó town ilu ondo jẹ́ ìlú kejì tí ó tóbi jùlọ ní ìpìnlẹ̀ ondo nigeria ìlú ondo jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìṣòwò fún agbègbè àwọn irúgbìn tí ìṣòwò gẹ́gẹ́bí iṣu gbágùdá ọkà tábà àti òwú ni a gbìn èyí tí a máa ń lò láti hun aṣọ pàtàkì ti àṣà tí a mọ̀ sí asọ òkè aṣọ èyí tí ó wọ́pọ̀ láti ṣé aṣọ láàrin àwọn olùgbé agbègbè ìlú òndó jẹ́ ol... |
lillian echelon mbadiwe lillian echelon mbadiwe jẹ́ òṣèrébìnrin àti oníṣòwò tó gbajúgbajà nínú iṣẹ́ fíìmù ṣíṣé látàri fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ black rose àmì-ẹ̀yẹ àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jù lọ ní amvca ti ọdún 2018 àmì-ẹ̀yẹ golden discovery actor ní gold movie award àmì-... |
aroko alarinyanjiyan aròkọ alárínyànjiyàn jẹ aroko ti a maa n se fami- n- fa lori lori koko oro kan yala lati segbe leyin re tabi tako o bi a ba n se aroko alariyanjiyan a ni lati maa fi si otun ki a si ma fi si osi ni ori koko oro naa nipa sise alaye anfani ati aleebu okookan nipa awon koko oro inu akori wa ninu aroko... |
àròkọ oníròyin àròkọ oníròyìn àròkọ oníròyìn jẹ́ àròkọ tí a fi ń ròyìn ìṣẹ̀lẹ̀ kan tí ó sojú ẹni tàbí èyí tí wọ́n sọ fún ni ṣé yorùbá bọ̀ wọ́n ni ohun tó ṣojú ẹni kì í sẹ̀yìn ẹni bẹ́ẹ̀ ni ìròyìn kò tó àfojúba ẹni tí ó dé ibẹ̀ ló lè sọ àpẹẹrẹ àròkọ oníròyìn ètò lẹrù igi ó ṣe pàtàkì nígbà tí a bá ń kọ àròkọ oníròyìn a gb... |
aroko onisorongbesi aroko onisorongbesi aroko onisorongbesi ni aroko ti a fi n se itakuoro so laarin eniyan meji tabi juu bee lo |
alo apamo alo apamo ni irufe alo ti o ni ibere ati idahun oju ese ninu apeere alo apamo alaye siwaju sii alo je ere ti wopo laarin awon omode ere osupa si ni pelu awon omode maa n kora jo lale lati se ere yii lati dekun ere asekudorogbo won a kora won lo sile agba to gbo aloo yanranyan lati gbo alo loore-koore lojo ro ... |
irenije ìrẹ́nijẹ ni ìgbésè fifún àwọn ọ̀wọ́ ènìyàn kan ní agbára láti lè gba agbára láti fẹ̀tọ́ àwọn mìíràn dùn wọ́n láti lè pa àwọn mìíràn lẹ́nu mọ́ àti làti lè gàba lé àwọn ọ̀wọ́ ènìyàn mìíràn oríkì yìí fihàn pé àwọn arẹ́nijẹ ni agbára èyí tí àwọn tí wọ́n ń hùwà ìrẹ́nijẹ sí kò ní agbára yìí ni ó sì ń fún wọn ní àǹfàn... |
aroko alariyanjiyan |
eye okin ẹyẹ ọ̀kín jẹ́ ọlọ́jà láàrin àwọn ẹyẹ ó jẹ́ arẹwà ẹyẹ pẹ̀lú oríṣìíríṣìí ìyẹ́ aláràǹbarà ní ara rẹ̀ ó jẹ́ ẹyẹ tí ó máa ń rìn ní orí ilẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni kì í sááàbá fò bí àwọn ẹyẹ yòókù takotabo ni ẹyẹ ọ̀kín kò sí ẹni tí yóò rí ẹyẹ ọ̀kín tí kò ní fẹ́ràn rẹ̀ nítorí ẹ̀bùn ẹwà tí elédùá fi jíǹkí rẹ̀ láàrin ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹyẹ |
ìwà ọmọlúàì etiquette is the set of norms of personal behaviour in polite society usually occurring in the form of an ethical code of the expected and accepted social behaviours that accord with the conventions and norms observed and practised by a society a social class or a social group in modern english usage the fr... |
unbreakable fíìmù nollywood unbreakable jẹ́ fíìmù ajẹmọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríà tó dá lórí baálé ilé kan tó ní láti kojú ìṣòro ààrùn ọpọlọ ti ìyàwó àṣẹ̀ṣẹ̀fẹ́ rẹ̀ buky campbell ló ṣàgbéjáde fíìmù yìí tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ ben chiadika sola osofisan ló sì kọ ọ́ oṣù kẹwàá ọdún 2018 ni wọ́n ya fíìmù yìí ní ìlú èkó à... |
oc ukeje okechukwu ukeje tí àọn ènìyàn tún mọ̀ sí oc ukeje jé òṣèrékùnrin ilẹ̀ nàìjíríààti olórin ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tó gba àmì-ẹ̀yẹ ti amstel malta box office ambo ó ti gba ọ̀pọlọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bí i africa movie academy awards africa magic viewers choice awards nollywood movies awards best of nollywood awards nigeria ... |
izu ojukwu izu ojukwu jẹ́ olùdarí fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2007 ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún ìsọ̀rí olùdarí tó dára jù lọ fún fíìmù sitanda ní àyẹyẹ ọlọ́dún kẹta ti africa movie academu award àmì-ẹ̀yẹ mẹ́sàn-án ni wọ́n yàn án fún àmọ́ ó márùn-ún ló gbà níbi ayẹyẹ náà |
arese emokpae agharese emokpae tí wọ́n bí ní january 13 1988 tí wọ́n mọ̀ sí a'rese jẹ́ òṣèrébìnrin akọrin àti òǹkàtàn ọmọ nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa nínú fíìmù bolanle austen-peters' terra kulture tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ wakaa the musical èyí sì mu kópa nínú ìdíje the voice nigeria tó sì jáwé olúborí ní ọdún 20... |
yinka davies yinka davies tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù keje ọdún 1970 jẹ́ olórin oníjó akọ-orin-kalẹ̀ àti adájọ́ ètò olórin ti nigerian idol ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà yinka ti wà nínú ilé-iṣẹ́ ìdárayá fún bí i ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n ìpìlẹ̀ rẹ̀ bàbá rẹ̀ ọmọ benin republic/ ìran líṣàbí ti ìlú sierra leonetó kó wá sí orí... |
john dumelo john dumelo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kejì ọdún 1984 jẹ́ òṣèrékùnrin àti olóṣèlú ilẹ̀ ghana ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹrin ọdún 2014 ó di ọmọ orílẹ̀-èdè ghana àkọ́kọ́ tó máa ní ìféràn mílíọ́ọ̀nù kan lórí facebook àwọn òbí rẹ̀ ni mr john dumelo tó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti mrs antoinette dumelo tó ń ṣịṣẹ́ pẹ̀lú customs... |
ìpínlẹ̀ ábíá |
ìpínlẹ̀ adámáwá |
ìpínlẹ̀ akwa íbọm |
ìpínlẹ̀ kébbí |
ìpínlẹ̀ tàràbà |
ìpínlẹ̀ anámbra |
ìpínlẹ̀ bàyélsà |
ìpínlẹ̀ bọ̀rnó |
ìpínlẹ̀ dẹ́ltà |
ìpínlẹ̀ ẹ̀bọ́nyì |
ìpínlẹ̀ ẹdó |
ìpínlẹ̀ ẹnúgu |
ìpínlẹ̀ gòmbè |
ìpínlẹ̀ ímò |
ìpínlẹ̀ jígàwà |
ìpínlẹ̀ kàdúná |
ìpínlẹ̀ kàtsínà |
ìpínlẹ̀ násáráwá |
ìpínlẹ̀ sókótó |
ìpínlẹ̀ yòbè |
mòrókò |
kẹ́nyà |
sẹ̀nẹ̀gàl |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.