raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
moses ọláìyá adéjùmọ̀ moses ọláìyá adéjùmọ̀ 1936 - 2018 je gbaju gbaja osere ori amohun-maworan ati oni sinima omo ile naijiria ohun ni opo eniyan mo si baba sala o je alawada kerikeri elere ori itage yoruba moses adejumo je omo ilu ijesha ni ipinle osunbaba sala ni a gba pe o je oludasile awada comedy ninu ere sinima ... |
moses olaiya |
hubert ogunde hubert adédèjí ògúnǹdé 31 may a bi ni odun 1916 o ku ni 4 april 1990 hubert adédèjì ògúnǹdé jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ati sinnimá àgbéléwò ọmọ yorùbá láti orílẹ̀ èdè naijiria ó tún jẹ́ olùkọ̀tàn olùdarí eré orí-ìtàgé akọrin òun ni olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèré ògúnǹdé kalẹ̀ èyí tí ó jẹ́ alákọ̀ọ́kọ́ irú rẹ̀ nílẹ̀ yorùb... |
orin juju |
orin jùjú orin jùjú tabi jùjú je iru orin agbo lati nigeria to wa lati iluorin asa yoruba |
patrice lumumba patrice émery lumumba 2 july 1925 17 january 1961 |
òfin mẹ́wàá àwọn ọ̀fin mẹ́wàá jẹ́ àkòjọ àwọn òfin mẹ́wàá ìwùwà tí bíbélì sọ pé ọlọ́run fún mose lórí òkè sinai nínú pátákó òkúta méjí àwọn òfin mẹ́wàá àwọn ẹsẹ òfin mẹ́wàá bí wọn ṣe wà nínú ìwé eksodu àti deuteronomi |
november 4 |
austríà austríà tabi lonibise bi orileominira ile austria german republik österreich je orile-ede atimo ile to ni awon eniyan bi egbegberun 88 to wa ni aringbongan europe o ni bode mo orileominira tseki ati jemani ni ariawa slofakia ati hungari ni ilaorun slofenia ati italia ni gusu ati switsalandi ati likstenstein ni ... |
september 4 |
november 28 |
swídìn swídìn tabi sweden je orile-ede ni europe |
gusau <ns>0</ns> <revision> <parentid>396728</parentid> <timestamp>2013-03-08t143219z</timestamp> <contributor> <username>addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> migrating 14 interwiki links now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> gusau je oluilu ipinle zamfara ni... |
abakaliki <ns>0</ns> <revision> <parentid>554990</parentid> <timestamp>2022-07-08t051713z</timestamp> <contributor> <username>ọmọladéabídèmí99</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> abakaliki je ilu ni naijiria ati oluilu ipinle ebonyi ni apa ila oorun |
birnin kébbí birnin kebbi je oluilu fun ipinle kebbi ni naijiria |
gòmbè gombe je oluilu ipinle gombe ni orile-ede naijiria |
dutse dutse ni olú-ìlú ìpínlẹ̀ jigawa ní ariwa nàìjíríà ibẹ̀ ni yunifásitì ìlú dutse tí wón dá kalẹ̀ ní oṣù kọkànlá ọdún 2011kalẹ̀ sí àwọn olùgbé dutse jẹ́ 153000 òun sì ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ jigawa |
kàtsínà katsina je ilu ni ile naijiria ati oluilu ipinle katsina ni apa ariwa |
jos jos ni olú ìlú ipinle plateau ní orílè-èdè nàìjíríà |
damaturu damaturu je ilu ni naijiria be sini otun je oluilu ipinle yobe |
jalingo jalingo ni olú-ìlú ìpínlẹ̀ taraba ní ariwa ìwọ oòrùn nàìjíríà jalingo ní èdè fulfulde túmọ̀ sí ibi gíga ó sì ní olùgbé 418000 àwọn fulani àti àwọn ẹ̀yà kẹ́kẹ̀ kẹ́ mìíràn ni ó wà ní ìlú jalingo fulfulde mumuye hausa àti àwọn èdè míràn ni wọ́n ń sọ ní jalin alámòjútó alága ìjọba ìbílè kọ̀ọ̀kan ní nàìjíríà lóní al... |
lafia capital city of nasarawa state nigeria lafia jẹ́ ìlú kan ní àárín gbùngbùn gúúsù ilẹ̀ nàìjíríà òun ni olú-ìlú ìpínlẹ̀ nasarawa ó sì ní àwọn olùgbé tí ó tó 330712 ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ní nàìjíríà sọ òun ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ nasarawa ìtàn àwọn míràn mo ìlú lafia sí lafian bare-bari muha... |
lọ́kọ́ja lọ́kọ́ja je oluilu ipinle kogi ni naijiria |
minna minna ni oluilu ipinle niger ni orile-ede naijiria |
sókótó sokoto je ilu pataki kan ni ariwa iwo oorun naijiria nitosi idapomora odo sokoto ati odo rima ni odun 2006 olugbe ti o wa ni be ju 427760 sokoto ni oluilu ipinle sokoto o si je oluilu awon ipinle ti o wa ni ariwa iwo oorun naijiria tele oruko sokoto oruko atijo re ni sakkwato ni ipilese larubawa je sooq ti o tun... |
iso 3166 iso 3166 je apa meta opagun amioro fun agbegbe lati se amioro fun awon orile-ede awon agbegbe to ba le won ati ipin apa won ti àgbájọ káríayé fún ìṣọ̀págun tesiwejade oruko re gangan ni awon amioro fun isoju fun awon oruko orile-ede ati ipinlabe won |
iso 3166-1 iso 3166-1 je amioro apa opagun iso 3166 fun ibudo lati se amioro fun awon orile-ede awon agbegbe to ba le won ati ipin apa won ti àgbájọ káríayé fún ìṣọ̀págun te jade oruko re gangan ni awon amioro fun ikosile awon oruko orile-ede ati ipin apa won - apa kinni awon amioro orile-ede eyi ni o se ala agbajo met... |
iso 3166 |
iso 3166-1 |
orílẹ̀-èdè orílẹ̀-èdè ni agbègbè tàbí ilẹ̀ kàn tí ó ní ààlà tí ó sì ní àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣe àkóso lórí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìjọba |
orile-ede |
ìjọba ìjọba ni ikorajo ninu awujo kan ile oloselu tabi agbajo to ni ase lati se ati fipase ofin ilana itele-ofin ijoba ntoka si ijoba abele isejoba oludalara to le ibile onibinibi tabi kariaye ìjọba je akojoegbe to n joba lori agbegbe iselu kan awon alase ninu awujo ati elo fun awon alase lati pase lori awujo |
itálíà itálíà ítálì tabi orílẹ̀-èdè olómìnira itálíà je orile-ede ni orile europe |
english language |
èdè igbo |
ipinle abia |
ipinle adamawa |
ipinle akwa ibom |
ipinle anambra |
ìpínlẹ anambra |
ipinle bauchi |
ipinle bayelsa |
ipinle borno |
ipinle cross river |
ipinle delta |
ipinle zamfara |
ipinle yobe |
ipinle taraba |
ipinle sokoto |
ipinle rivers |
ipinle plateau |
ipinle osun |
dakar dakar je oluilu orile-ede senegal |
nairobi nairobi ni oluilu orile-ede kenya ni iha ila orun afrika |
kampala kampala jẹ́ olú-ìlú orílẹ̀-ẹ́dẹ̀ uganda |
líbyà libya je orile-ede ni ariwa afrika |
apáìwọ̀orùn sàhárà apáìwọ̀oòrùn sahara je agbegbe ni ariwa afrika ti o ni bode pelu mòrókò ni ariwa algeria ni ilaoorunariwa ati guusu okun atlantiki ni ilaoorun |
ọjọ́ àbámẹ́ta |
wiki wiki |
web browser web browser ẹ̀rọ afọ̀nàhan web ètó ẹ̀rọ-ònkà ìsíwò ojúewé aláùntakùn a web browser is a software application which enables a user to display and interact with text images videos music games and other information typically located on a web page at a website on the world wide web or a local area network text ... |
ìsirò statistiki ìsirò statistiki |
olusẹgun obasanjo |
adesoji aderemi |
tanzania tànsáníà tabi orílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan ilẹ̀ tànsáníà pípè /ˌtænzəˈniːə/ <ns>10</ns> <id>12795</id> <revision> <id>534721</id> <parentid>473798</parentid> <timestamp>2020-05-23t231720z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wik... |
síríà síríà lárúbáwá sūriyya or sūryā lonibise bi orileominira arabu siria lárúbáwá al-jumhūriyyah al-ʿarabiyyah as-sūriyyah jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apá ìwòorùn asia ó ní ibodè pẹlú lebanon àti omi-òkun mediteraneani ní ìwọ̀oọ̀rùn turkey ní àríwá iraq ní ìlàoòrùn jordan ní gúúsù àti israel ní gúúsù-ìwọ̀oòrùn |
haile gebrselassie haile gebrselassie haylē gebre silassē ojoibi april 18 1973 je ara ethiopia asareidaraya ona jijina ati isare ojuona o gba eso wura olympiki meji fun 10000 metres ati ife-eye idije agbaye merin fun ijinna kanna o bori ni berlin marathon lemerin leralera ati dubai marathon lemeta leralera bakanna o tu... |
ará ethiopia |
ìbejì àwọn ìbejì jẹ́ àwọn ọmọ méjì tí ìyá wọn lóyún papọ̀ wọ́n lè jẹ́ obìnrin meji ọkùnrin méjì tàbi ọkùnrin kan àti obìnrin kan àwọn ìbejì le ti àti inú ẹyin kan jade tàbí láti inú ẹyin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ àwọn tí ó jáde láti inú ẹyin kan ma ń jo ara wọn wọ́n sì ma ń jẹ́ ọkùnrin méjì tàbí obìnrin méjì ní igbamiranìṣẹ̀lẹ̀ yí kò... |
anwar el sadat muhammad anwar al sadat 25 december 1918 - 6 october 1981 jẹ́ olóṣèlú àti ààrẹ ilẹ̀ egypti láti 5 october 1970 títí dé 6 october 1981 |
írẹ́lándì apáàríwá irẹlandi apáàríwá jẹ́ orílẹ̀-èdè ní ìsọ̀kan ilẹ̀-ọba tó fìhà sí ìláoòrùn-àríwá erékùsù irẹlandi |
bíbélì mimọ <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2008-10-01t082638z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>bíbélì mimọ moved to bíbélì mímọ́</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
bibeli mimo |
bibeli |
ẹ̀sìn krístì ẹ̀sìn kristi tàbí ìsìn kristi tàbí ẹ̀sìn onígbàgbọ́ tí àwon míràn máa ń pè ni ẹ̀sìn kiriyò jẹ́ ẹ̀sìn ọlọ́runkan tọ́ dá l'órí ìgbésíayé àti àwọn ẹ̀kọ́ jesu ti nasareti gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe kọsílẹ̀ nínú májẹ̀mú tuntun ti bíbélì ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ló fẹ́rẹ̀ tan kálẹ̀ jù ní gbogbo àgbáyé ní bíi nkàn an ọdún bíi mewa ... |
ilé-ìṣọ́ bábẹ́lì ilé-ìṣọ́ bábẹ́lì |
kùránì kùrání jẹ́ ìwé mímọ́ ẹ̀sìn islam |
kùrání |
james brown james joseph brown jr may 3 1933 december 25 2006 je olorin omo ile amerika |
yayi boni thomas yayi boni ọjọ́ìbí 1 july 1952 jẹ́ gbajúmọ̀ onímọ̀ ìfowópamọ́ àti òṣèlú àti ààrẹ orílẹ̀-èdè benin láti ọdún 2006 sí 2016 ó gba ìjọba lẹ́yìn tí ó wọlé nínú ìdìbò ààrẹ ti orílẹ̀-èdè benin lọ́dún 2006 bẹ́ẹ̀ náà lótún wọlé lẹ́ẹ̀kan si lọ́dún nínú ìdìbò ààrẹ orílẹ̀-èdè náà lọ́dún 2011 ní àkókò yìí òun ni wọ́... |
ìpínlẹ osun |
ipinle ekiti |
babatunde fashola babatunde raji fashola tí a bí ní 28 june 1963 jẹ́ agbẹjọ́rò àti olóṣèlú órílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti fìgbà kan jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ èkó fún sáà méjì láti ọdún 2007 sí ọdún 2015 lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́-òṣèlú all progressives congress olóyè bola tinubu ni ó jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ èkó ṣáájú rẹ̀ lodun 2015 ààrẹ muhammadu... |
bọ́lá tinúbú bọ́lá ahmed tinúbú ọjọ́ ìbí ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ́ta ọdun 1952 jẹ́ ààrẹ orílẹ̀-èdè nigeria tí wọ́n ṣe ìbúra fún lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2023 lẹ́yìn tí ó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ ọdun 2023 ó jẹ́ gómìnà-àná ìpínlẹ̀ èkó láàrin ọdún 29 may odun 1999 títí di ọdún 29 may 2007 àwọn ará ... |
gani fawehinmi ganiyu oyesola fawehinmi ọjọ́ ìbí ọjọ́ kẹjì-lé-lógún oṣù kẹrin ọdún 1938 - ṣe aláìsí ní ọjọ́ kárùn-ún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 2009 jẹ́ akòwé iṣẹ́ ajàfìtàfìtà ẹ̀tọ́ ènìyàn àti àgbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ gani jẹ́ ọmọ saheed àti munirat fawehinmi ti òndó ní ìpínlẹ̀ òndó ch... |
tai solarin augustus taiwo tai solarin tí wọ́n bí ní 20 august 1916 tó sì ṣaláìsí ní 27 july 1994 fìgbà kan jẹ́ olùkọ́ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ài òǹkọ̀wé ó ṣe ìdásílẹ̀ mayflower school ní ikenne ní ìpínlẹ̀ ògùn ní ọdún 1956 ní ọdún 1952 solarin di ọgá ilé-ìwé molusi college ní ijebu igbo ó sì wà ní ipò yìí títí wọ ọdún ... |
lagelu <ns>0</ns> <revision> <parentid>519363</parentid> <timestamp>2018-08-01t065853z</timestamp> <contributor> <username>adefanike</username> </contributor> <comment>mo fi ìtókasí kun oju ewe yi</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> lágelú ni ìtàn sọ pe o da ìlú ìbàdàn sílẹ̀ ìtàn fi ye wa wíp... |
sir ahmadu bello |
ọmọ haúsá <ns>0</ns> <revision> <parentid>459802</parentid> <timestamp>2023-01-26t193145z</timestamp> <contributor> <username>kwamikagami</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ọmọ hausa je |
ọ ọ ọ je alfabeti yoruba a b c d e ẹ f g gb h i j k l m n o ọ p q r s ṣ t u v w x y z |
fínlándì finlandi pipe fun onibise bi orile-ede olominira ile finlandi je orile-ede nordik kan to budo si agbegbe fennoscandia ni apaariwa europe o ni bo de mo sweden ni iwoorun norway ni ariwa ati russia ni ilaorun be sini estonia wa ni guusu re niwaju ikun-omi finlandi |
finland |
irak irak tabi orile-ede olominira ile irak |
iraq |
saddam hussein saddam hussein abd al-majid al-tikriti april 28 1937 december 30 2006 ni aare ile irak lati july 16 1979 titi de april 9 2003 |
olu falae samuel oluyemisi falae cfr ọjọ́ọ̀bí ọjọ́ kọkànlélógún oṣù ọ̀wàrà ọdún 1938 tí a mọ̀ sí olu falae jẹ́ òṣìṣẹ́ iléeṣé - ìfowópamọ́ alákòóso àti olóṣèlú láti àkúrẹ́ ìpínlẹ̀ òǹdó akọ̀wé ìjọba ológun babaginda ni lọ́dún january 1986 sí december 1990 ó sì jẹ́ mínísítà owóńná fún àsìkò ránpẹ́ ní ọdún 1990 ó díje dupò... |
olu falae |
ngozi okonjo-iweala nigerian economist ngozi okonjo-iweala tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 1954 jẹ́ onímọ̀ ètò ìṣúná ó sì tún jẹ́ alákòóso fún ètò ìnáwó àti alákòóso fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè tẹ́lẹ̀ fún orílẹ̀-èdè njíríà ó jẹ́ ìkan láàárín àwon adarí ni standard chartered bank twitter global alliance for vaccines an... |
september 21 <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2008-10-08t231634z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>redirecting to 21 september</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
ellen johnson-sirleaf ellen johnson-sirleaf ojoibi 29 september 1938 ni aare ile liberia lowolowo |
greece |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.