raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
nọ́mbà aṣẹ́kù |
nomba adogba |
nomba aseku |
daniel olorunfẹmi fagunwa |
ernest shonekan ernest adégúnlé oládéìǹdé shónèkàn ọjọ́ kẹẹ̀sán oṣù ebi ọdún1936 ní èkó orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ agbejọ́rò ará ilẹ̀ nàìjíríà shónékà jẹ́ ààrè ilè nàìjíríà fún ìgbà díẹ̀ láti ọjọ mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ́jọ ọdún 1993 títí dé ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1993 tí ọ̀gágun sani abacha fipa gbà joba lọ́w... |
bingu wa mutharika bingu wa mutharika 24 february 1934 6 april 2012 je oloselu ara malawi ati aare ile malawi lati 2004 di 2012 nigba to se alaisi |
dean barrow |
jigme khesar namgyel wangchuck jigme khesar namgyel wangchuck dzongkha ojoibi 21 february 1980 ni druk gyalpo ile bhutan ikarun oba ile bhutan ati olori ilé-oba wangchuck o gori oye ni 14 december 2006 o si gbade ni 6 november 2008 |
jigme thinley jigme yoser thinley ojoibi 1952 lo ti je alakoso agba orile-ede bhutan lati april 2008 won mo si lyonchen jigme yoser thinley lyonchen tumosi alakoso agba |
evo morales juan evo morales ayma ojoibi october 26 1959 to gbajumo lasan bi evo ni is the 80th and current aare 80k lowolowo orile-ede bolivia lati odun 2006 |
nikola špirić |
željko komšić |
nebojša radmanović |
haris silajdžić |
luiz inácio lula da silva luiz inácio lula da silva ojoibi 27 october 1945 o gbajumo gege bi lula ni aare orile-ede brazil lati 2003 titi 2011 a tún yàn sípò ààrẹ fún sáà kẹta ni odun 2022 tí à sì ṣe ìbúra-wọlé fun ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 2023 oun ni ààrẹ orílè-èdè brazil lọ́wọ́ lọ́wọ́ |
hassanal bolkiah |
georgi parvanov georgi sedefchov parvanov bùlgáríà ojoibi 28 june 1957 ni aare ile bulgaria lati 22 january 2002 |
boyko borisov |
tertius zongo tertius zongo ojoibi 18 may 1957 ni alakoso agba orile-ede burkina faso lati june 2007 |
than shwe than shwe θáɴ ʃwè ojoibi 2 february 1933 ni olori orile-ede myanmar |
thein sein thein sein ojoibi 1945 ni alakoso agba ile burma fun ibise myanmar lowolowo |
norodom sihamoni norodom sihamoni ojoibi 14 may 1953 ni oba orile-ede kambodia |
hun sen hun sen |
paul biya paul biya oruko abiso paul barthélemy biya'a bi mvondo 13 february 1933 lo ti je aare ile kameruun lati 6 november 1982 |
philémon yang philémon yunji yang ojoibi june 14 1947 je oloselu ara kameruun ati alakoso agba ile kameruun lati 30 june 2009 |
stephen harper stephen joseph harper pc mp ojoibi april 30 1959 ni alakoso agba 22ji lowolowo orile-ede kánádà ohun na tun ni olori egbe oloselu conservative party |
pedro pires pedro verona rodrigues pires ojoibi 29 april 1934 ni aare orile-ede cape verde lati march 2001 ki o to di aare ohun ni alakoso agba lati 1975 de 1991 |
josé maria neves josé maria pereira neves ojoibi march 28 1960 ni erekusu santiago ni alakoso agba ile cape verde ni oṣu kẹwa ọdun 2021 josé maria neves ṣẹgun idibo alakoso ni yika akọkọ ti oṣu kẹwa ọjọ 17 ni ibamu si awọn abajade akọkọ ti a tẹjade lori oju opo wẹẹbu osise bori 515 ti idibo opo to peye lati dibo ni yik... |
françois bozizé françois bozizé yangouvonda bíi ọjọ́ kẹrinla oṣù kẹwá odún 1946 jẹ́ ààrẹ orílè-èdè olómíníra àárín áfíríkà |
faustin-archange touadéra faustin-archange touadéra ojoibi april 21 1957 lo je alakoso agba orile-ede olominira arin afrika lati january 2008 |
idriss déby general idriss déby itno lárúbáwá idrīs daybī itnū ọjọ́ìbí june 18 1952 - 2021 ni olóṣèlú ará tsad tó tún jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ tsad 1990-2021 |
youssouf saleh abbas youssouf saleh abbas ojoibi c 1953 je oloselu ara tsad to je alakoso agba ile tsad lati april 2008 de march 2010 teletele o ti je onimoran diplomati ati asoju fun aare idriss déby |
michelle bachelet verónica michelle bachelet jeria /βeˈɾonika miˈʃɛl baʃˈle ˈçeɾja/ ojoibi september 29 1951 je oloselu ati aare orile-ede tsile tele — obinrin akoko lo je ti o gun ori ipo yi ni itan orile-ede na lati 11 march 2006 titi di 11 march 2010 |
wen jiabao wen jiabao ojoibi 15 september 1942 ni alakoso agba orile-ede olominira awon ara saina lati 2003 |
álvaro uribe orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè spéìn àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni uribe èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni vélez álvaro uribe vélez ojoibi 4 july 1952 ni aare ile kolombia 58k lati 2002 de 2010 |
ahmed abdallah sambi |
denis sassou-nguesso denis sassou nguesso ojoibi november 23 1943 je oloselu ara kongo to ti je aare ile kongo lati 1997 o tun je aare tele lati 1979 de 1992 ni oṣu kẹwa ọdun 2021 denis sassou n'guesso ni a mẹnuba ninu itanjẹ ti “awọn iwe pandora” ni ibamu si ajọṣepọ agbaye ti awọn oniroyin o wa ni ọdun 1998 ni kete lẹ... |
joseph kabila joseph kabila kabange lasan bi joseph kabila ojoibi 4 osu kefa 1971 ni aare ti orile-ede olominira toseluarailu ile kongo ootk lati 2001 ti de 2019 o bo si ori aga ni osu kinni odun 2001 ojo mewa leyin iku oloro to pa baba re laurent-désiré kabila to ti je aare ootk ni 27 osu kokanla 2006 joseph kabila je... |
adolphe muzito adolphe muzito ojoibi 1957 in gungu igberiko kwilu ni oloselu ara kongo oot lowolowo to je alakoso agba orile-ede olominira toseluarailu ile kongo muzito omo egbe oloselu egbe lumumbisti piparapo palu teletele ti je alakoso isuna labe alakos agba antoine gizenga lati 2007 de 2008 muzito to wa lati gungu ... |
óscar arias óscar rafael de jesús arias sánchez ojoibi 13 september 1940 je oloselu ara orile-ede kosta rika to di aare ile kosta rika lati odun 2006 de 2010 teletele o tun je aare lati 1986 de 1990 o si gba ebun nobel ni 1987 fun iyanju re lati mu opin ba awon ogun abele ti won nlowo nigbana ni opo awon orile-ede aari... |
stjepan mesić stjepan stipe mesić ojoibi december 24 1934 ni aare orile-ede kroatia tele lati 18 february 2000 di 18 february 2010 bakanna o tun je alakoso agba ile kroatia akoko lati 30 may 1990 de 24 august 1990 |
jadranka kosor jadranka kosor ojoibi july 1 1953 je oloselu ati oniroyin tele ara orile-ede croatia o di obinrin akoko to je alakoso agba ile kroatia ni july 6 2009 leyin igbati ivo sanader to je alakoso agba tele kosesile |
raúl castro ọ̀gágun-ẹlẹ́ẹ̀ṣọ́ tifeyinti raúl modesto castro ruz ojoibi 3 june 1931 ni aare ile kuba lati 24 february 2008 o hun ni aburo fidel castro |
dimitris christofias dimitris christofias also demetris gíríkì is a left-wing greek cypriot politician and was sixth president of the republic of cyprus |
václav klaus václav klaus ojoibi 19 june 1941 ni aare orile-ede tseki olominira lati 2003 o tun je didiboyan ni 2008 bakanna ohun tun lo je alakoso agba ile tseki tele 19921997 o je onimo oro-okowo |
jan fischer olóṣèlú ilẹ̀ tṣẹ́skì jan fischer ojoibi 2 january 1951 lo je alakoso agba orile-ede tseki olominira lati osu karun 2009 titi di 13 osu keje 2010 |
jan fischer czech politician |
margrethe keji ile denmark margrethe keji margrethe alexandrine þórhildur ingrid tabi nigba niran bii margaret keji ojoibi 16 april 1940 ni ayaba orioye orile-ede denmark |
lars løkke rasmussen lars løkke rasmussen ojoibi 15 may 1964 ni alakoso agba orile-ede denmark |
ismail omar guelleh ismaïl omar guelleh somali ismaaciil cumar geelle arabic اسماعيل عُمر جليه ojoibi november 27 1947 ni aare orile-ede djibouti |
dileita mohamed dileita dileita mohamed dileita lárúbáwá ojoibi march 12 1958 ni alakoso agba orile-ede djibouti lati march 2001 |
nicholas liverpool nicholas joseph orville liverpool ti a bi ni september 9 1934 grand bay dominica ku june 1 2015 miami florida usa jẹ alakoso dominika lati ọdun 2003 titi di ọdun 2012 |
roosevelt skerrit |
leonel fernández leonel antonio fernández reyna ojoibi 26 december 1953 ni aare orile-ede dominiki olominira lati 2004 wa |
josé ramos-horta josé manuel ramos-horta born 26 december 1949 is the president of east timor the second since independence from indonesia taking office on 20 may 2007 je eni to gba ebun nobel alafia |
xanana gusmão kay rala xanana gusmão oruko abiso josé alexandre gusmão ojoibi 20 june 1946 je alagidi ogun tele to di aare akoko ile ilaorun timor lori aga lati may 2002 de may 2007 leyin re o tun di alakoso agba ile ilaorun timor ni 8 august 2007 titi doni |
rafael correa rafael vicente correa delgado ojoibi april 6 1963 ni aare orile-ede olominira ile ekuador lati 2007 ati lowolowo aare pro tempore isokan awon omoorile-ede guusu amerika onimo oro-okowo to keko ni ecuador belgium ati us o je fun igba soki bi alakoso inawo orile-ede re ni 2005 o je didiboyan bi aare ni opin... |
hosni mubarak muhammad hosni sayyid mubarak lárúbáwá muḥammad ḥusnī sayyid mubārak ojoibi 4 may 1928 - 25 february 2020 je aare kerin orile-ede orileolominira arabu ile egypti lati 14 october 1981 leyin iku aare anwar el-sadat titi de 2011 ohun ni olori orile-ede egypti to pejulo lori aga lati igba muhammad ali pasha |
ahmed nazif ahmed nazif lárúbáwá born july 8 1952 in alexandria served as the prime minister of egypt from 14 july 2004 to 29 january 2011 when his cabinet was dismissed by president hosni mubarak in light of a popular uprising that led to the egyptian revolution of 2011 nazif was acting president of egypt from 5 mar... |
mauricio funes |
teodoro obiang nguema mbasogo orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè spéìn àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni nguema èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni mbasogo teodoro obiang nguema mbasogo ọjọ́ìbí 5 june 1942 ni olóṣèlú ará guinea ibialágedeméjì tó ti jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ gínì ibialágedeméjì láti ọdún 1979 ó fi ipá gba ìjọba lọ́wọ́ arákùn... |
ignacio milam tang orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè spéìn àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni milam èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni tang ignacio milam tang ọjọ́ìbí 20 june 1940 ni olóṣèlú ará gínì ibialágedeméjì tó jẹ́ alákóso àgbà ilẹ̀ gínì ibialagedeméjì láti osù keje ọdún 2008 di osù karùún ọdún 2012 ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ọ̀ṣèl... |
isaias afewerki |
andrus ansip andrus ansip ojoibi 1 october 1956 ni o je lowolowo alakoso agba orile-ede estonia |
girma wolde-giorgis girma wolde-giorgis ojoibi december 1924 ni addis ababa ni aare orile-ede ethiopia lowolowo lati october 8 2001 |
meles zenawi meles zenawi asres ge'ez መለስ ዜናዊ አስረስ mäläs zenawi äsräs 8 may 1955 20 august 2012 abiso bi legesse zenawi asres ni alakoso agba orile-ede ethiopia lati 1985 ohun ni alaga tigrayan peoples' liberation front tplf ati lowolowo olori ethiopian people's revolutionary democratic front eprdf |
epeli nailatikau epeli nailatikau lvo obe msd ostj ojoibi july 5 1941 bakanna bi na turaga mai naisogolaca je oloye ni fiji ati lowolowo aare ile fiji |
frank bainimarama |
tarja halonen ojoibi 24 december 1943 ni aare ikokanla ati lowolowo bayi orile-ede finland ohun ni obinrin akoko lori ipo yi teletele halonen je ikan ninu omo ile igbimo asofin lati 1979 de 2000 nigbato fisile leyin idiboyan re gege bi aare |
matti vanhanen matti taneli vanhanen ojoibi november 4 1955 ni alakoso agba ile finland lati 2003 titi di 2010 ati alaga egbe oloselu keskustacentre party of finland tele ni apa keji odun 2006 o je aare igbimopo europe teletele o je oniroyin ise vanhanen je bibi ni jyväskylä omo ojogbon tatu vanhanen to je ekeji-olukow... |
françois fillon françois charles amand fillon ojoibi 4 march 1954 ni le mans sarthe ni lowolowo alakoso agba ile fransi o je yiyansipo latowo aare nicolas sarkozy ni ojo 17 may 2007 o koko kosesile bi alakoso agba ni 13 november 2010 ki kabineti o to je tuntunda ni ojo 14 november 2010 aare nicolas sarkozy tunyansipo p... |
ali bongo ondimba ali-ben bongo ondimba oruko abiso alain bernard bongo ni february 9 1959 je oloselu ara gabon ti n se aare orile-ede gabon lowolowo leyin ibori re ninu idiboyan aare 2009 idiboyan aare 2016 |
paul biyoghé mba paul biyoghé mba ojoibi 18 april 1953 je oloselu ara gabon to je alakoso agba ile gabon lati july 2009 o je omo egbe gabonese democratic party pdg o ti wa nipo alakoso ninu ijoba ko to di pe won yan gege bi alakoso agba |
yahya jammeh yahya abdul-azziz jemus junkung diliu jammeh ojoibi may 25 1965 ni aare orile-ede gambia |
mikheil saakashvili mikheil nikolozis dze saak'ashvili ojoibi 21 december 1967 je ara orile-ede georgia oloselu ohun ni aare ile georgia lowolowo |
nikoloz gilauri |
horst köhler horst köhler ojoibi 22 february 1943 ni heidenstein generalgouvernement skierbieszów loni poland je oloselu ara jẹ́mánì ti isokan toseluaralu elesinkristi ati aare ile jemani lati 2004 de 2010 |
angela merkel angela dorothea merkel omo kasner ojoibi 17 july 1954 ni kansilo orile-ede germany |
karolos papoulias karolos papoulias gíríkì ojoibi june 4 1929 - oṣu kejila ọjọ 26 ọdun 2021 ni aare orile-ede griisi |
tillman thomas tillman joseph thomas ojoibi june 13 1945 je oloselu ara grenada to je alakoso agba ile grenada lowolowo ohun tun ni olori national democratic congress ndc |
tupac shakur tupac amaru shakur june 16 1971 september 13 1996 jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká olórin ọmọ ilẹ̀ amẹẹ́ríkà tí orúkọ ìnagijẹ̀ rẹ̀ ń jẹ́ 2pac tàbí pac lásán tàbí makavẹ́lì ó jẹ́ olórin ráápù tí ó kú ní ọdún 1996 |
orin rap |
álvaro colom álvaro colom caballeros ojoibi 15 june 1951-23 january 2023 ni aare orile-ede guatemala fun igba 20082012 ati olori egbe oloselu alawujo-toloseluarailu national unity of hope une |
moussa camara moussa dadis camara ojoibi 1964 je oga ologun tele ni ise ologun ile guinea to di aare orile-ede guinea fun national council for democracy and development conseil national de la démocratie et du développement cndd eyi to fi tipatipa gba ijoba ni 23 december 2008 leyin iku aare lansana conté o ti kuro lori... |
kabiné komara kabiné komara ojoibi 1950 won tun pe oruko lorisirisi ona bayi kabinet kabineh kabinè is je alakoso agba orile-ede guinea ijọba ti ọdun 2021 ni oṣu kẹwa ọdun 2021 kabiné komara mu atilẹyin rẹ wa si ijọba ijọba ti o ṣe ikọlu ijọba ni guinea |
malam bacai sanhá malam bacai sanhá 5 may 1947 9 january 2012 je oloselu ara guinea-bissau to ti je aare ile guinea-bissau lati 8 september 2009 |
carlos gomes júnior carlos domingos gomes júnior ojoibi december 19 1949 ni alakoso agba ile guinea-bissau teletele o je alakoso agba lati 10 may 2004 de 2 november 2005 o si tun je yiyan si ipo yi ni 25 december 2008 |
bharrat jagdeo bharrat jagdeo tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kíní ọdún 1964 jẹ́ ̀aàrẹ orílẹ̀-èdè guyana láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹjọ ọdún 1999 ó jẹ́ alákòóso ètò ìṣúná kí ó tó di ààrẹ lẹ́yìn tí ààrẹ janet jagan kúrò nípò |
sam hinds samuel archibald anthony hinds ojoibi 27 december 1943 je oloselu ara guyana to je alakoso agba ile guyana lowolowo fun igba die o je aare ile guyana lati 6 march 1997 de 19 december 1997 |
rené préval rené garcia préval born january 17 1943 je oloselu ara orile-ede haiti to je aare orile-ede haiti lati may 2006 de 14 may 2011 teletele o tun ti je aare lati february 7 1996 titi di february 7 2001 ati gege bi alakoso agba lati february 1991 titi di october 11 1991 |
jean-max bellerive jean-max bellerive ojoibi 1958 ni alakoso agba orile-ede haiti lowolowo |
roberto micheletti roberto micheletti bain bibi 13 august 1943 di aare ile honduras ni 28 june 2009 fun igbadie o fi ipo sile ni january 27 2010 ni gba ti porfirio lobo sosa gun ori aga gege bi aare |
porfirio lobo sosa porfirio lobo sosa ojoibi 22 december 1947 mimo bi pepe lobo ni aare ile honduras oloselu ati adako |
lászló sólyom lászló sólyom january 3 1942 october 8 2023 aare ti hungary laarin 2005 ati 2010 |
gordon bajnai |
ólafur ragnar grímsson president of iceland 1996-2016 |
jóhanna sigurðardóttir |
alẹksándrọ̀s olókìkí aleksandros iii oba áwọn ará makedoni 356323 sk to gbajumo bi aleksandros olokiki èdè grííkì ayéijọ́un je gíríkíi› oba basileus ile makedoni to da ile-oba titobijulo ni igba ijohun |
alexander the great |
continent |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.