text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
ọlọ́run ùn mi ọba òkè ògo ni fún orúkọ elédùmarè ọba adániwáyé mágbàgbé ẹni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí la wá ń work! 🇳🇬 #AyajoOjoAwonOsise #MayDay
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
beeni o bi a se n baa lo yii afaimo ki awon atohunrinwa ma gbalu mo wa lowo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí a bá wò ó, à á rí pé ó ní ìdí tí a fi ka èèwọ̀ yìí lákọ̀ọ́kọ́. #eewo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Aku ojumo oni, ojumo ire o""""""""@user: """"""""Jíjí tí mo jí lóòwúrọ̀, mo bẹ Elédùmarè báabá bá mi ṣé... """""""" Ẹ mà mà káàárọ̀ o ẹyin …
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ jẹ́ a ṣe rere láyé, kí a bá j'èrè l'ọ́run. Ẹ jẹ́ ká ṣ'ayé ire, torí ònìí kọ́, nítorí ọ̀la ni, torí àtunbọ̀tán.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ògbójú ode nínú igbó irúmalè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n tún ní bíbọ̀ bíbọ̀ ni t'ẹ̀bọ̀yè. A tọ̀ Ọ́ wá fún àbò tó ní'pan jùlọ. #ekaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
iṣẹ́ èwe bẹ àgbà kágbà má ṣe kọ̀ mọ́ gbogbo wa la níṣẹ́ a jọ ń bẹra wa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
irú ilà ojú wo ni pélé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò ṣe ìṣedúró. 'Ẹ́fà' jẹ́ ìbànújẹ́ ọgbẹ́- Síbẹ̀ àwàdà agbára míràn tí kìí ṣe ẹ̀rín
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ajé Olókun ò! Ilé èmi kiní yìí ni kí o máa bọ̀, agbe gbé e kò mí tààrà, má gbée yà bàrà síbìkan. #Ire16
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ti eyan BA FI tipa BA omo, molebi, tabi ARA e lopo, ki lo ma se? #MarchAgainstRape #TweetYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Màálù tí ò ní 'rù , Ọlọ́hun ní í báa lé eṣinṣin ni wá, ẹ dákun ẹ ṣe wá dáradára bí ẹ ṣe fẹ́ kí wọ́n ṣe síi yín. #Nigeria @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Europe kẹ́rú, wọ́n kó ẹrù, wọ́n ńṣe yàlàyòlò, wọ́n ńṣe bí ọlọ́ba. Wọ́n f'ọrọ̀ tí wọ́n jí níbi tún ọ̀dọ̀ wọn ṣe. #OminiraNigeria #Jegudujera
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#TweetinYoruba Iwa awon omo Naija to ba dibi ounje https://t.co/j9zgsHhnNu https://t.co/pKKNOpP3Dn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àlàáfíà bá mi ṣe ajé bá mi ṣe ire gbogbo wá bá mi ṣe ìyẹn lọ́jọ́ òní àti nígbà gbogbo títí láéláé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user . Ejeki a ki eni wa @user Omo Olojoibi ku ori ire oni ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré àgbéléwò ti Nàìjíríà tó dára ni èyí. . . . Ogun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní orílè-èdè Nàìjíríà yìí jẹ́ rògbòdìyàn tí kò dára, eré yìí fi ìhà búburú orílè-èdè yìí hàn. Erè tó ní ìjà ni.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: 7. Tú ìsúnkì kẹta palẹ̀ : Lérímọ̀ = lórí ewé imọ̀ ọ̀pẹ Pàjùbà = pa àjùbà Ṣánkọ = #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aré àná kò tán síbẹ̀ o àti ṣì máa dìbò lónìí èkó ò ní bàjẹ́ o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ mà kú ọjọ́ mélòókan o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abala karùn-ún. A kò gbo̟dò̟ dá e̟nì ké̟ni lóró tàbí kí a lò ó ní ìlò ìkà tí kò ye̟ o̟mo̟ ènìyàn tàbí ìlò tó lè tàbùkù è̟dá ènìyàn.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orí ooo! Orí hu! 🙌🏾 #Orí #cultotradicionalyoruba #yoruba https://t.co/hndpdWKOgT
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A #Yoruba #Poem - Ise Logun Ise ~ With #English Translation - #xpino #SCHOLARS https://t.co/NNtbyKoJi3 #Education #Nigeria #Lagos
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
what is the name of the yorùbá deity that is known for treating people with herbs and leaves kíni orúkọ òrìṣà yorùbá tí ó ma ń tọ́jú èèyàn pẹ̀lú ewé àti egbò
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user emi mo igbalo o, ounje to dun gba ni, kolorun ma pa iya baba mi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo ojú kọ́ ló ńṣe ipin; gbogbo igi kọ́ ló ńhu olú. / Not all eyes are rheumy; not all (dead) trees sprout mushrooms. [No hasty generalisations: you can't tar everyone (or everything) with the same brush; appearance can be deceptive.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àbá 2 - Ọmọdé ló ń bọ̀ wá dàgbà, kò síhun burú nínú ká máa bá àwọn èwe wa sọ̀rọ̀. Kájọ dá yẹ̀yẹ́, tàkọ̀rọ̀sọ ní tọmọ sí òbí. #Abameta
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pèrègún tí ń bẹ lódò kìí kú. Bẹ́ẹ̀ ẹiyẹ odídẹrẹ́ kìí kú sóko ìwánkanjẹ. ♫ Ikú yẹ̀ lórí mi...♫
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user ti ko ni da bi eni wipe mo na Ku pro laarin, ejowo iwé WO ni e nsòrò nípa o? #TweetYorubaFriday
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilẹ̀ àánú Olúwa kì í ṣú. / God's mercy never runs out. [No impossibility with God: He cannot be contained or cornered; keep hope alive.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni bá nbẹ̀rẹ̀ sí ísùnlọ́, tí ntají, tí nsùnlọ, tí ntají, kí ló nṣe? #ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìgbà òjò tí à ń palẹ̀ oko mọ́ nìkan kọ́ ni à ń ṣe eré bí obìrin onípò bá yúnsẹ̀ òrìṣà ní àsìkò ọ̀gbẹlẹ̀ tí ọ̀dá òjó bá wà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
BÍ ÀWỌN YORÙBÁ ṢE PÍN ÀSÌKÒ ÒJÒ Òjò Agẹmọ (òkudù-Agẹmọ) - ojo tí ó ma ń fi ojojúmọ́ rọ̀ ní rẹpẹtẹ. Òjò yìí ma ń rọ̀ ní àsìkò ọdún Agẹmọ Òjò Òwòrẹ́ - Òjò tí ó ma ń rọ̀ díẹ̀ díẹ̀ tí ó sì lè yọ oòrùn tí ó bá yá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""Mo kí ìyáálé ilé kan pẹ̀lú ọ̀wọ̀ níjọ́sí, Mo ní 'Ẹ pẹ̀lẹ́, mà!', Ó bá bínú, ó ní 'Mo jẹ́gbẹ́ ẹ kọ́ bùọ̀dá'... Ó ṣe mí ní…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user eyi ni a n pe ni alaagomeji!!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀yin aṣojúu wa ni #NationalConference, ẹ ṣe bó ti tọ́ àti bó ti yẹ o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹni tó bá ní kí ọ̀rẹ́ òun má jọba ni kò ní lọ̀rẹ́ ọba whoever blocks his friend from becoming a king wont have a k
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ire loju owo ri, ni re ni re lo ng soro atare. Ire aaro, osan ati ashale je ko je temi loji.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abala ko̟kàndínlógún. E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ sí òmì nira láti ní ìmò̟ràn tí ó wù ú, kí ó sì so̟ irú ìmò̟ràn bé̟è̟ jáde; è̟tó̟yìí gbani láàyè láti ní ìmò̟ràn yòówù láìsí àtakò láti ò̟dò̟ e̟nìké̟ni láti wádìí ò̟rò̟, 1/2
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó dára gan-an ni, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ pé gbogbo abala ere náà ló gbádùn.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
o fẹ́ fọ iléè rẹ mọ́ má ṣòpò rìn jìnà pé affairs sóríi ẹ̀rọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò burú fún àgbéyẹ̀wò
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ọmọ Yoòbá pọ́mbélé gbòde. Ẹ yáa súré tete tẹ̀lé --->@user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nítesíwájú sí i àkọsẹ̀jáyé ẹni ní ṣàlàyé ẹgbẹ́ tí ẹní tọ̀ wá ṣáyé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ikan laa fowo mu.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tó ńlé ará iwájú, èrò ẹ̀hìn ńtọ̀ òun náà lẹ́hìn. / Whoever is pursuing those ahead, is also being pursued by those…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó rẹwà, ó gbà gbogbo ọkàn, ó lágbára, ó le.. . . . Fíìmù yí ṣe àfihàn gbogbo àwọn ìṣòro tí àwọn ọmọ ayé òde òní ni ilẹ̀ Nàìjíríà ń kojú kò kàn fi ọwọ́ ba ohun kankan lérèfé. Yóò mú inú bí ọ làwọn ibì kọ̀ọ̀kan. Yóò ru ọ nínú sókè ní èyí tí mo rò pé ìdí tí wọ́n fi ṣe é náà nìyẹn. Láti jẹ́ kí àwọn tí ó wò ó gbé ìgbésí ay...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ ka alẹ́ o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
toh a ma be obe ni be isu atelese abenowo eni to ba ni kama bo la ni deba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
we appreciate everyone on the team for making this happen ẹ ṣeun o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ká dúpẹ́ lọ́wọ́ ọrùn tó gbé orí dúró ọ̀pọ̀ ẹran ló sún mọ́ orí tí ò ṣe nǹkankan we ought to be thankful to the neck f
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó yẹ láti wò. . Ṣètò lòdì sí ẹ̀hìn ìgbìyànjú ìṣọ̀tẹ̀1976 ní Nàìjíríà èyí jẹ́ fíìmù tí ó dára. Kò ní ìwọ̀n tí ó pọ̀ ṣùgbọ́n eré tí ó dára ní.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ko fi ile wa se ibugbe lose tuntun yi RT""""""""@user: Ajé o!""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kaada fun Osi. 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #hausa… https://t.co/r4PmWiv6X4
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
níyanjú jẹ́jẹ́. Bíbẹ̀rẹ̀ dáradára ṣùgbọ́n ó bàjẹ́ bí ó tí ń ṣiṣẹ́ gùn jù fún àwọn oníìwé-dára.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Koje ki aye o gun https://t.co/cbeXNj4ZIB
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gẹ́gẹ́ bí onígbá iyùn ṣe dá a lábàá wípé kí n máa sọ ìdáhùn ìbéèrè tí ẹnikẹ́ni kò bá gbà bí ó bá di agogo mẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eranko wo ni à ń pè ní àjànà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àjọ elétò ìdìbò #Nigeria #INEC ò ṣé e 're l'Ékòó o. Àwọn ọmọ Èkó ò rí káàdì ìdìbò gbà fún ọjọ́ mẹ́ta. Ṣé a ò ní dìbò l'Ékòó ní 2015 ni?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré tí o dára .
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
10. Igi gbígbẹ ò ṣe é tẹ̀ ní kọ̀ngọ́. Òwe àwọn àgbà ni. Ọmọ Yoòbá, jọ̀wọ́ kíni ìtumọ̀ òwe yìí? #Ibeere #Yoruba #Owe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ku ọdun tuntun. Happy new year. #Yoruba https://t.co/GyBe13FyNL https://t.co/ovQC3BiPVR
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ti a ba wo ohun ti awon wooli aye ode oni so fifi ede fo daa le pe ogede naa benitori wipe kiko ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí a tó ó ṣe iṣẹ́ kan tàbí òmíràn, ẹ jẹ́ kí bèrè lọ́wọ́ orí, kí Ajé ba bá wa gbé. Ire Ajé o! #IgbagboYorubaNipaAje
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Efere"""" kìí ṣe Yorùbá. Èdè Efik ni. Orúkọ ẹ̀ ní Yorùbá ni """"Papasan""""--> http://t.co/TNnRmDjP http://t.co/AfuQKPrZ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn tí a gbélẹ̀ ni ọ̀nà tó yàtọ̀ . . Eléyìí jẹ́ eré àgbéléwò to múná-dóko . Wo eré yìí pẹ̀lú inú kan.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Inú mi dùn nígbà tí ọ̀dọ́mọdé kan ládùúgbò fi ara tuntun tí ó fi aró dá sára aṣọ hàn mí. #YeMaaSun #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ gbọ́ kí ni yóò ṣẹlẹ̀ sí wọn ní ọ̀túna? #keresimasi http://t.co/YTePEablwI
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
amin oooire ni tiwa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eji kí o yáa rọ̀ síi o ni o! A nílò rẹ, kí ohun ọ̀gbìn ó ba a ta, kí oúnjẹ ba a pọ̀ jamùrá. #IjebuLahun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Parí òwe yìí #owé #yoruba https://t.co/nUF0bxNdqY
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Okunrin gbongbonran bi oranmiyan #yoruba https://t.co/yZ4FK0xG7a
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo wa la mo pe ole ofon kiolohun kigbe ni omobirin deziani sugbon ko sese ko ji owo to to $bn in ill naigiri
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó jẹ́ ìdẹ̀rúbà àti ojú ayé pẹ̀lú ẹ̀rù tí ń rákò tí ó lọ́ra tí kò sanwó gaan ní ìparí.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ ye é ba orúkọ Yoòbá jẹ́, ẹ̀yin aráa wa lórí ayélujára -> Facebook #Twitter #LinkedIn #Pinterest #foursquare #KoOrukoDaadaa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀kúnwọ́ wọn jẹ́ ọmọ pàápàá àwọn ará díẹ̀ láti àti ibòmíràn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹ yéé gbé ọmọ Ọbà f'Ọ́ṣun! Ẹkùn kọ́ ni Tiger, ẹní bá dé ààfin ọba yóò rí ohun tí wọ́n ń pè ní ẹkùn (ògìdán). Ìkòrikò (ìkòo…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ènìyàn funfún wà lórílẹ̀ eèpẹ̀ lóòótọ́? Ènìyàn dúdú ńkọ́? Níbo ni àwọn ọ̀rọ̀-ìperí wọ̀nyí ti ṣẹ̀ wá? Nítorí èmi kò rí ènìyàn funfun àti dúdú rí o, àbí ẹyin rí i irú ènìyàn ọmọ adáríhurun bẹ́ẹ̀ rí? Ẹ jẹ́ n gbọ́.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ mélòó ni O'òduà bí? Dárúkọ wọn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àmì ohùn èdè yoòbá ohùn ìsàlẹ̀ dò ohùn àárín re àti ohùn òkè mí sùn sun sún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ ṣeun tí ẹ dara pọ̀ mọ́ wa. Ẹ jọ̀wọ́, kí a tó bẹ̀rẹ̀ ètò ní pẹrẹwu, ẹ bá wa júwèé ara yín fún gbogbo ilé. Orúkọ yín, àti ibi tí ẹ ti ń kàn sí wa. Thank you for joining us. Before we proceed in full gear, kindly do a short introduction of yourself to the house
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo nǹkan tó jẹ́ dúdú ò dára, wọ́n ti gbin ìgbìnkugbìn síwa lọ́kàn. | #TransAtlanticSlaveTrade #OwoEru
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Fagi lé - To cancel Àpẹẹrẹ: Wọ́n fagi lé ìpàdé náà - They canceled the meeting #learnyoruba #yorubaidioms #onlineyoru…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Queen Salawa Abeni for the night! """"""""Sebi l'ọfe l'ọfe ni Baba fun wa Sebi l'ọfe l'ọfe ni Baba fun wa o Iṣẹ́ Olúwa, àwòyanu n…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user obo (do re) ni aaya amo mi o mo ogungbe.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Kòkòrò tó ńjó lẹ́ẹ̀bá ọ̀nà, onílù rẹ̀ ńbẹ nínú igbó. / The insect that is dancing by the bush path has its drummer rig…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èyí a ṣe yẹn náà tó ìyókù di ìdájí ọ̀la kí ẹlẹ́mìí má gbàá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó kéré ju ti àtẹ̀yìnwá lọ. Wọn kò ṣeé dáadáa. Ó dàbí pé oṣù kan ni wọn fi ṣeé sugbọn ó dájú pé baba ńlá aláìní ọpọlọ rárá ní
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
bí o kò bá gbàgbé ìṣẹ̀lẹ̀ láabi àná yóò fàfarapa fún òníì rẹ bẹ́ẹ̀ yóò sì bá ọjọ́ ọ̀laà rẹ jẹ́
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
how dumb does it sound for a person calling for division and waryou and what weaponswán pa gbogbo yin dánu get aks get sophisticated weaponskoni kaluku farabale ko ronu
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣọ̀ún ni ọba ìlú Ògbómọ̀ṣọ́ #Ogbomoso #Yorùbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pẹ̀lú àwọn kùdíẹ̀káàtóo Nollywood, Jẹ́ kí á ya ìtàn náà
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ara fu ènìkan tí ó rí arábìnrin ajọ́mọgbé ọ̀hún, ìwé pélébé tí máṣànfàní fi parọ́ wípé òṣìṣẹ́ ìjọba lòun. #Obalende http://t.co/uPTFfIszME
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Jẹ ki ohun gbogbo ti o li ẹmi ki o yìn Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Oluwa. #ORIN_DAFIDI 150,6. #Yoruba #Psalms """"""""""""""""Que todos os sere…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ajá bá wọ́ agbádá iná, tí àmọ̀tékùn w'ẹ̀wù ẹ̀jẹ̀, tí ológìnní wo'so èkísà, apanije ni gbogbo wọn. The dog may wear a fiery dress while the leopard dresses in red blood, the cat may appear in a tattered dress, they are all carnivores. #Yoruba #Heritage
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Awa ni Iran ti ayan.. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Omo Igbala Ke Halleluyah #Praise #Naijapaise #praiseandworship #Yoruba #omoigbala #iwillpraise #glory #halleluyah #rccg #SolidRockPeople #solidminstrels #worship #worshipper https://t.co/VaM6jgaGMr
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user àgó tó gbó̩n ṣáṣá ikú pa á, àńbèlèntàsé ọ̀pọ̀lọ́ tí ń janra rẹ̀ mọ́lẹ̀.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train