text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Ó fẹ́ẹ́ ṣègbọ̀nsẹ̀, owó ni. Da pàntí nù, owó ni Bólà àti LAWMA ń gbà. Ó fẹ́ẹ́ dáná, wà á ra afẹ́fẹ́ ìdáná, epo parafín. #owoekoekolongbe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
9. Ìyàtọ̀ wo ló wà láàárín aṣọ òfì àti aṣọ òkè? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èèyàn ò sunwọ̀n láàyè; ọjọ́ a kú là ńd'ère. #yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àsopọ̀ àti àwọn ìyípadà ko dan tàbí ojúlówó ..
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
A ti wà ní gbàgede #SakaraFiesta2017 ní #FreedomPark. #Yoruba https://t.co/pNebagGr4f
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọpẹ́lọpẹ́ ọmọ-ogun Ìbàdàn, ì bá má sí ọba aládé tó jẹ́ Yorùbá níbi kankan ńlẹ̀ káàárọ̀-o-ò-jí-ire mọ́. #ItanFulani #Darandaran #Nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ayé ò ní burú fún wa olódùmarè á fi wá lọ́kàn balẹ̀ ẹ kú ojúmọ́ o ẹ̀yin ọ̀rẹ́
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èje dínkan, ọ̀ṣẹ̀ kan ò pé mọ́. Òní ló pé ọjọ́ mẹfa tó kù láti fí iṣẹ rẹ ranṣẹ sí wa ní https://t.co/phydI214HF Send in your Submission now. #AtelewoPrize #Yoruba #Atelewo https://t.co/d2i81F0X7p
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: @user Ire o."""""""" Ire ni ao ma jii rii..ki eledumare fi opolopo ire shamona fun wa o..assee :-)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pápàpá iṣẹ́ tòní ń tán lọ. Ó wá ku fàájì pẹrẹhu. Àríyá kẹlẹlẹ.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìpàdé wa bí oyin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user didake GEJ jasi pe oro omiyale ti di ko kan mi ati pe boya awon alatako lo wa ni 'di omiyale gege bi ifehon ...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: B'a a lowo B'a a niwa Owo olowo ni Iwa loba awure Eyin mutumuwa,e toju iwa yin @user @user @user @user…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bó pẹ bó yá, ogún ọdún ńbọ̀ wá k'ọ̀la. (Twenty years time will one day be referred to as tomorrow.) #yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí ewé ṣe tóbi tó kọ́ ló ṣe wúlò tó how big a leaf is is not necessarily how useful it is appearance can be dec
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oṣù karùn-ún ọdún 2018. Ire ọwọ́ a bí márùn-ún jèrè àrún ni tia lóṣù Èbìbí yìí. A óò dá bí ẹdun, a ó rọ̀ bí òwè láṣẹ Ọba-Òkè. #May #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ní abọ̀òṣà ni wá, a ò m'Ọlọ́run, ọpọlọ wa dúdú. ##ItanOduduwaBeeniBeeko
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
inú ọgbà la wà fún ayẹyẹ àyájọ́ ọjọ́ yorùbá ẹgbẹ̀rún kan naira lowó ìwọlé ìwọ́ náà máa bọ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orò baba ò!"""" #IkoroduOga #Agemo #Eyibi #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
isokuso gba ni oro ogidi omo yoruba ni ko je lowo si nnkan to ma tabuku sile yoruba ifowowewo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹṣin ọ̀rọ́ ní 'a kì í dúró kí wọn n'Ífẹ̀ Ọọ̀ni, bẹ́ẹ̀ a kì í bẹ̀rẹ̀ kí wọn n'Ífẹ̀ Oòyè, bí a bá dúró kí wọn n'Ífẹ̀ Ọọ̀ni ńkọ́? #asaikini
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bi awon olote fe, bi won ko, Ama de ibi ti afe de. Efi ye wan pe, bi awon olote fe, bi won ko, orilede #Nigeria a de i…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kòóòkó jànánjànján bẹ̀rẹ̀, ìsinmi parí. Ọba Òkè máà jẹ́ kí wàhálà wa ó já sásán. Ẹ máa yáṣẹ́ o! https://t.co/KbGyUzEdst
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Yorùbá adage for the week: """"""""Ìrírí ayé ò ní t'ini títí kó t'ini pa, ọgbọ́n ló fi ń kọ́ni"""""""" Translation: Challenges and exp…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pistle gun is ìbọn ìléwọ́ in Yorùbá #yoruba #LearnYoruba http://t.co/B4ahTq3U1b
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Òkóbó ò le è fi alátọ́sín șẹ̀sín. Òwe míì fún ọ̀ràn Ọọ̀ni àti Elékòó. #Yoruba #Oduduwa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ami eye kankan ko to si wa ipalemo wa ko munadoko rara a ṣánpá lọ ṣánpá bọ̀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Eewo. Oluwa o ni fun won se.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Yoruba Ohun obinrin yii sọ pe ki i ṣe arun Korona, #Covid19 lo paayan rẹpẹtẹ ni Kano, bikoṣe ẹrọ #5G. """"""""Ẹrọ yii ni wọn tan ina si ni Kano to bẹrẹ si i pa gbogbo wọn."""""""" Ohun ti obinrin naa sọ ree Irọ funfun balau Ẹ ka a lori: https://t.co/6VjAElikID
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n fi ère pe eré, wọ́n pajá lọ́bọ, wọ́n fi itọ́ funfun sínú, tu pupa síta, nítorí ìfẹ́ ara ti wọn nìkan. #OminiraNigeria #NigeriaAt56
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ekaro gbogbo ile. Ajire bi? https://t.co/XDws0frtvY
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
keep the answers coming will mark them soon so as to keep the participation active we appreciate your responses so far a ma fi èsì sí àwọn ìdáhùn yín láìpẹ́ kí àwọn ẹlòmíràn náà lé è kópa nínú ìdáhùn yìí a nífẹ̀ẹ́ sí àwọn ìdáhùn yín
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Dandan ni bíbọ Ògún nítorí pé, nígbàtí irúnmọlẹ̀ ń tìkọ̀lé ọ̀run bọ̀ wá sílẹ̀ Ifẹ̀, Ògún l'ó la Ọ̀nà dé Ifẹ̀. #Olojo #IleIfe #Yoruba #Isese
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òní ni àgbáyé ńsàmì àyájọ́ ọjọ́ òṣìṣẹ́, mo kí ṣiṣẹ́ṣiṣẹ́ gbogbo, iṣẹ́ wa ò ní d'ìṣẹ́ o. Àmín àṣẹ. #AyajoOjoIsese #LabourDay #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Owo omode ko to pepe, ti agbalagba k'owo keregbe #yoruba #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èjìlù àti málàkì wá bẹ ọmọlẹ́bí wọn olúgbani olorì àdó wó àmọ́ ìròyìn ọba ti wàjà ni wọ́n dé bá àna wọn ti dòrìṣà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aago mejila nko ti roorun sun Ibere oso ni eleyii o ... *mikanle*
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Rabone Bros, N.M. Rothschild & Sons. Aṣe ọkọ̀ ojú omi, William Moore, De Beers, John Gladstone ló ti ìdí okòwò ẹrú la bẹẹrẹ.#OIANUK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Ota ilosiwaju nikan ni ko nii ri ohun meremere tijoba Aregbesola ti se l… https://t.co/VAVe69p2RY
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Awa niyen jare a ku isinmi opin ose""""""""@user: @user mo ti n tele e o, oshay omo iya mi""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
11. #PariOweYii: Méjì ló yẹ á bá lọ s'ógun... #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user Inu wa oba de dun ti eba je ikan ninu awon atokun @user ati se ikilo tele 👇 https://t.co/wyr3HWq6uo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: God no go let us jam Agbako o, abi wetin this bird gain now? 🙄 #voiceover #yoruba 18+ 18+ https://t.co/FbekrbVBFv
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a má ńkóo létíi ajọ̀ọ gaàrí a ó tẹ̀ ẹ́ mọ́wọ́ fi iyọ̀ pa á yanán a ó sì fi àgbọn jẹ ẹ́ bí a bá fẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Gbúre. Ng kò mọ nkan tó njẹ́ """"""""""""""""Efere"""""""""""""""". Mo lérò pé èdè Efik ni, kìí ṣe Yorùbá.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹ wá ba mi re! #yorubafood #naijafood #africanfood http://t.co/T32HYEPg4M
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Njẹ́ jíjí tí mo jí, ma súré tete ṣèbà Elédùà, Ọba Alágbára ńlá. Ọba Ṣèyíówùú. Kááábíèsí o! #TwitYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user eba wa se alaye owe Yoruba ti o so wipe """"""""""""""""Omo eni ku, o san ju omo eni nu lo"""""""""""""""" fun Aare @user ki wan se awon odomobirin #ChibokGirls ati #DapchiGirls ni awa ri. Oro ki ajini gbe pelu ipa ti wa di nkan nla bayi, jake jado Nijeria. Eyin adari eranti ikunle abiyamo o https://t.co/CXJIy7k...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ká ṣiṣẹ́ ká lówó kò dàbí ká mowó ná translation knowing how to earn cannot be compared to knowing how to spend lesson it is important to take note of our spending habits
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ifá ⏩ Bara Àgbọnnìrègún Èṣù ⏩ Ẹlẹ́gbára Ògún ⏩ Lákáayé Yẹmọja ⏩ Àwòyó #Yoruba #Orisa https://t.co/6WHsU6WsQp
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aarẹ @user ni awọn akẹkọ Dapchi yoo gba itusilẹ. Ẹ gba ijọba ni imọran lori ọna ti wọn le gba tete ri awọn ọmọ naa gba pada.https://t.co/HEbcnxJcBr
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user E ma seun o! Odun uo a da fun wa o!"""" Àmín ẹ̀ pọ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn iléìjọ́sìn àdáyébá pọ̀ ní àdúgbò yìí kílódé tí wọn ò kọ́lé báyìí mọ́ gbogbo ti ìgbàlódé ló tètè ń wó lulẹ̀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Gbogbo àwọn tó nsọ #norwegian ò ju iye àwọn tó ngbé ìlú Èkó lọ! http://t.co/5AOwMUKG
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Atayán yán eléyìí ṣò wọ́n , ṣùgbọ́n bí ati ríi nínú eré àgbéléwò aládùn tí a ṣètò dáradára tí ó si fani móra yìí, àṣà ati ìṣe àwọn ènìyàn ti a korira yii sèfárahàn ti o ye .
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bẹ́ẹ̀ ni tì Ẹ rí, Ọba Àjọkẹ́ ayé, O ṣéun, mo kẹ́ Ọ. Ọ̀gbààgbà, O ṣé tó O gbà mí, O pè mí láláàyè. Mo kíra sí Ọ Ọ̀gàá Ńlá. Kábíèsí o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìsẹ̀yín ni adarí ìjọìsìn ìjọọba ìjọẹgbẹ́ ń fi ọ̀bẹ ẹ̀yìn bu iṣu gbogbo ọmọ ìjọ arálùú ẹgbẹ́ jẹ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀rọ̀ náà ta kókó a ò rójútùú ẹ̀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ogbólògbó ajà fún ẹ̀tọ́ @user ṣe àtakò ìjọba #Nigeria ní ìlú #Berlin #WhereIsOurMoney #OwooWaDa http://t.co/Mq4RH0pfVn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user E le ta recipe na fun awon ile ounje Naija.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ráńṣẹ́ sí àwọn ẹ̀gbá láti ti ọwọ́ ọmọ wọn bọ aṣọ kí wọ́n padà sí ìlú wọn ajá ní ń wí ẹran ní ń sọ̀rọ̀ ni àwọn ẹ̀gbá fi ọ̀rọ̀ ìjọba britain ṣìí àbùkù ò ní ilé ibikíbi nií ti ń dé bá ni lálejò ni ìjọba britain fi èsì ẹ̀gbá ṣe ní britain bá gbé
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Akọ àti abo. Abórí àti adárípọ́n. Ìwàlẹ̀ àti___ #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó ku ọ̀kan méjì ni ìbéèrè sọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àṣẹ̀hìnwá àṣẹ̀hìnbọ̀, ohun tí wọ́n sọ fún wa wípé àwọn fẹ́ ṣe kọ́ ni wọ́n ṣe. #Nigbatiwonde
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọdún Ògún ni a máa ń ṣe ní sáà tí a wọ̀ yìí kí èèbó tó ó gbé ti wọn dé, èyí ni a fi pe oṣù 8 ni Ògún. #OsuOgun #Yoruba #August #InYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
inú òjò ni alàgbà ma ń ṣeré kiri oòrùn ló jẹ́ kó ba sábẹ̀ igi torípé kò fẹ́ràn an oòrùn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bótilẹ̀jẹ́pé iṣẹ́ àárín jẹ́ ìwúnilóri àìsè àìbalẹ̀ àìbìkítà tí àgbẹ̀ bigbé rì ìtàn tí ó fanimọ́ra náà, tí ó jẹ́ kí ó jẹ́ wíwú tí ó nira púpọ̀ ju tí ó nílò láti jẹ.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: O fẹ mu, ko ma le mu o... @user @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user iṣẹ́ lo ṣe bọ̀bọ́ o! 👍🏿 #CashAndCarryPrison
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
THE ITEMS USED IN IFÁ CONSULTATION (1): IKÍN ÌYẸ̀ROSÙN ỌPỌ́N IFÁ ODÙ IFÁ AWON OHUN ÈÈLÒ IFÁ DÍDÁ: IKÍN ÌYẸ̀ROSÙN ỌPỌ́N IFÁ ODÙ IFÁ Our guest for today @user, will explain how these items are used and, the process involved in generating an ODÙ IFÁ, using them. https://t.co/k4TdLoYPJm
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀rẹ́ mi àtàtà ni ń ṣe bíi tiyín èé ti rí tẹ bèrè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ORÍṢI ỌJÀ ỌJÀ ONÍGBÀ: àwọn ọjà wọ̀nyìí ma ń wáyé ní òòrèkóòrè ní àwọn ìlú kékeré, ìgbèríko tàbí ìlú tó ní èrò díẹ̀. Ọjọ́ márùn-ún ni wọ́n ma ń ná àwọn ọjà wọ̀nyìí. Ní àwọn ibòmíràn, ọjọ́ mẹ́sààn-án ni wọ́n ma fi ń ná wọn. Ọjọ́ ọjà òmíràn ma ń bẹ̀rẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
‘House of Talents’ jẹ́ ilẹ̀ àwọn ohun ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀. Àwọn òșèré yẹn kò rí i ṣe rara
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
CLANS AND THEIR HERITAGE NAMES / Ẹ̀YÀ YORÙBÁ ÀTI ORÚKỌ ÌṢẸ̀M̀BÁYÉ WỌN (2): Ọ̀GBÓMỌ̀ṢỌ́ ọmọ Ajílété Ọ̀YỌ́ ALÁÀFIN ÌJẸ̀BÚ ọmọ AJAGBALÚRA ÒSOGBO ÒRÒKÍ ÈKÓ ÀKÉTE ÌKÒRÒDÚ Ọ̀GÀ ÌKÀRẸ́ OLÓKÈ MÉJÌ TAKỌ TABO ÒNDÓ EKÍMÒGÚN
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwon ti ìlàje yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
omi ìnira ọrọ̀ ajé orílẹ̀èdè nàìjíríà ń ṣe òjòjò owó oṣù òṣìṣẹ́ ò tó nǹkankan rà oúnjẹ hán gógó ta la á gbà wá
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
IPA TÍ ÀMÌ OHÙN-ÚN Ń KÓ NÍNÚ-U GBÓLÓHÙN-UN YORÙBÁ Bí a bá fẹ́ sọ gbólóhùn tí ó jẹ mọ́ nǹkan ẹni, bóyá nǹkan ti ẹnìkìíní, ẹnìkejì tàbí ẹnìkẹ́ta, ki ní náà tí ó jẹ́ ohun ìní ẹni yóò fa ọmọ-ọ̀rọ̀ ìyẹn fáwẹ̀lì tí ó kẹ́yìn gùn. #Ami #Yoruba #LearnYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Owó ẹyọ dídà fún Ifá ni à ń pè ní ẹẹ́rìn-dín-lógún. #OwoEyo tí a ti dálu mẹ́rin dín ní ogún ni à ń lò. #Yoruba https://t.co…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ki odun tuntun ye wa sowo ki oye wa si omo ki o gba wa lowo akindanidani oba nebukudeneza ilu nijeria ki jamba boko haramu dekun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ káàárọ̀ o, ẹ si kú déédé ìwòyí. Iba ò ní pa wá laì pẹ ọjọ́. Àmín. Àṣẹ #yoruba #WorldMalariaDay #endmalaria #RollBackMalaria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user Adupe lowo Olodumare fun abo Ategun oru eni ni ilu oba po sugbon Oluwa ko je ki a…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Irọ́ ni @user àti àwọn ilé isẹ́ oníròhìn bẹ́ẹ̀ máa ń pa nípa ilẹ̀ adúláwọ̀. Àfikún àti àsọdùn wọ́n pọ̀. #MediaImperialism #Ghana
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lori ijinigbe ni Dapchi: Ileesẹ ologun jẹwọ. Ẹ ka ijẹwọ naa nibi: #BBCYoruba https://t.co/XFggqKRbXn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Njẹ o mọ iwọn otutu ti ara giga le jẹ ami ibẹrẹ ti coronavirus? Ṣayẹwo iwọn otutu rẹ loni lati tete mo bi ilera ara re se ri. #coronavirus #Yoruba https://t.co/hccFPIFMe1
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lẹ́yìn àwọn ìbejì táíyé kánhìn ó kan ìdòwú ó kan àlàbá orúkọ àmútọ̀runwá wo ló kàn lẹ́yìn àlàbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
“Ẹ dúró ẹ róṣọ, ẹ dè wá o! Ìwòran ẹ máà yìí lọ! “ #Gelede
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bi Olode O ba Ku...... Ojude E Kogbodo Wu Gbegi (koriko)
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kánkán l'ewé iná ń jó'mọ Iná yóò jó o yín pa Wàràwàrà l'ọmọ í t'oko ìṣíbọ̀ Ilé ò gbá ọ̀nà ò gbà á ní í ṣe ewé àháràgbá Ilé á lé e yín, ọ̀nà á nà yín Àtilọ àtibọ̀ kì í jẹ́ kí àgánrándì ó gbádùn Ìnira ni ti yín, ẹ ò ní gbádùn #EpeForOurGovernment
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwa méjì la jọ ni í, bí ẹnìkíní ba lo o, a a gbéeélẹ̀ kẹ́nìkejì ó lò ó. Àwa àti àwọn ọmọ la ni ọmú. #AyewoOmu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
T'ó bá jẹ́ látijọ́ ni, òjò l'á á jí wa láàárọ̀ yìí. A kú oṣù titun t'ó wọlé dé. Òkúdù á gbé wá o! #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
with passion gan pàápàá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fun mi ni anfaani leekan pere mo seleri pe o ko ni kabamo pe o se temi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Good evening @user, we welcome to the house, tonight. And, we are glad to have you here. Please, before we proceed, let the audience know you. Ẹ kúu alẹ́ @user, a kíi yín káàbọ̀ sórí ètò wa ni àṣálẹ́ yìí. Inú wa dùn láti ní yín. Ẹ jẹ́ kí àwọn ará ilé mọ̀ yín
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọmọ Èkó pàdánù ẹ̀mí, ọba Kòsọ́kọ́ sá lọ Àpápá. #Apapa ni Kòsọ́kọ́ bá wọ Ẹ̀pẹ́. #Lagos #OgunAhoyaya #Yoruba https://t.co/Z633qDrLGF
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kíni ìtàn yí kọ́ wa? #Itanilumasee #yobamoodua
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÒKÈ OLÓSÙNTA Òkè mímọ́ ní Ìkẹ́rẹ́ Èkìtì, tí àwọn ará ìlú náà gbàgbọ́ wípé, ó jẹ́ ilé fún Òrìṣà Olósùnta. Ọjọ́ méje ni wọ́n fi ma ń ṣe ọdún ìbọ Òrìṣà náà, ní ọdọọdún. https://t.co/U2qNZADpgb
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user eni osi se yo ma jale!!!""""IṢẸ́ ÀGBẸ̀ N'IṢẸ́ ILẸ̀Ẹ WA #Ise #Agbe #Yoruba #Nigeria #yobamoodua
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìbà làá kọ́ọ́ jú mo ṣe ìbà olódùmarè ìbà gba rúnmọlẹ̀ ojú kọ̀tún ojú kòsì ìbà ọ̀kànlénírinwó irúnmọlẹ̀ ìbà ọkùnrin tobìnrin ìbà ẹlẹyẹ ìbà ọmọdé ìbà àgbà ìbà oyún inú ìbà àsẹ́ìbí ìbà àwọn tí wọ́n ti dá kí n tó dá ìbà àwọn tí wọ́n ti tẹ̀ kí n tó tẹ̀ ìbà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user @user @user @user Adupe lowo Oosa Oke Fun Ase…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ń jẹ́ Àkúrẹ́ ní ìparí 1890 síwájú Orísun ìmọ̀ yìí: Adebanji Akítóyè (2014), A HISTORY OF THE YORÙBÁ PEOPLE, Amalion Publishing, Dakar. Abala 233
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train