text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Ẹlẹ́rìí, @user ní nísojú òun ni àwọn ọlọ́pàá NSCDC #Apo ti ń lu @user àti #Briggs bíi gbẹ̀du #ReleaseOmojuwaAndBriggsNow
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Iyanu l'oruko re iyanu l'oruko re Baba mi to n se ohun t'eni kan o le se iyanu l'oruko re......
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a kò gbọdọ̀ tìtorí kòkòrò kó síni lójú kí a wá ki igi bọ ojú ọ̀hún you shouldnt poke a stick into your eye simply because an insect entered it be moderate adopt extreme measures with caution
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
amin ni oruko awimayewun beno ni ko ri fun ogbeni alakowe yoruba loni ati lailai
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Boya o ti to asiko lati se apero ni orilede wa Lori Owo idagbasoke ile iwe giga
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
John Gladstone l'ó kó owó tí a fi kọ́ ojú irin Liverpool sí Manchester sílẹ̀. #OIANUK #BlackHistoryMonthUK https://t.co/iI5PK92tVB
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀yin ọmọ mùsùlùmí òdodo ẹ kú ọdún ìtunu àwẹ̀ ah àṣèyíṣèmíì tọmọtọmọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
7• Ẹdìẹ ìrànà, kì í ṣe oúnjẹ àjẹgbé. Kíni adìẹ ìrànà? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú ojúmọ́ o ẹ̀yin sànmọ̀rí. A ò ní dààmú o. Orí wa á kànkè lọ́la Ọba Òkè.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọba máà jẹ́ a r'àrìn f'ẹsẹ̀ sí o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹfin. *Ẹfin ni àwọn Yorùbá ń pe àwọ̀ tí ẹ mọ̀ sí purple lédèe Gẹ̀ẹ́sì. Láyé àtijọ́, a ní irú aṣọ àrán kan tí ó jẹ́ aláwọ̀ọ ẹfin, àrán ẹfin sì ni wọ́n ń pè é. #learnyoruba #Language https://t.co/Rp67sGdlvn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bákan náà, tí alábaraméjì tí ó diwọ́ disẹ̀ sínú bá re ọ̀run, dandan gbọ̀n ni, a ó ṣe orò fún un. #AsaOro #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ajé olùpèsè ọrọ̀ kú ojúmọ́ o ajé ìwọ làjíkí ìwọ làjíkẹ̀ ìwọ làjípè ìwọ ni mo mú ṣokùn ajé ìwọ ni mo mú ṣedẹ ìwọ ní í fi ẹni iwájú sílẹ̀ ṣe tẹ̀yìn lóore ajé ṣe mí lóore ọlá ọlà àti arísìkí ọrọ̀ sọ mí dajífọwọ́bajé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aago márùn-ún ti lù. Àsìkò ìbéèrè yá. Ta ló máa gba ìbéèrè mẹ́wàá, kí ó gba owó ìpè ọgọ́rùn-ún náírà? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user. Ogun o ran won mo. Sugbon abe mosquito neti.ti wo fi ogun re ni awa sun ni ile wa. A ko gburo yamuya ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àgbọn olódu máa ń so ọmọ àmọ́ kò sí ohun tí a lè jẹ nínú rẹ̀ bíi àgbọn abo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user oko labo simi oko nigbati ile ba ri bayi o. #mounreringan
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ise ni ogun ise mu ra si se ore mi ise lafi deni giga bi a ko ba re ni feyin ti bi ole lari bi a ko
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eyin temi eku ojumo, emi eyan yin ogbeni Oladapo Omo Olanrewaju Omo bibu ilu eko Ni isale eko,eko mi eko ti ee, eko Oni baje #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ́rí, ní nǹkan bíi 1853, """"""""Bí-Ọlọ́run-pẹ̀lú"""""""" ni à ń pe ìlú Lànlátẹ̀? #Oyo #Yoruba https://t.co/DliOhEZ2gm
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
*O ní bí ọba bá w'àjà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O mọ eégún t'ó ma ń mú pàṣán lọ́wọ́? O mọ pàṣán? Aago 1 #Eegun #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹní bá purọ́ á á jalè whoever lies habitually will steal nip those moral failings in the bud they hardly rema
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
The future looks bright, even in Black n White. #ReinventHER #newgist . Happy Hump day Gistas mi ọ̀wọ́n ṣe dede ẹ jọ̀? . . #lifeofagista #ondo #yoruba #4decadesoffavor #makingyoulaughseriously #laughnigeria… https://t.co/nH5mobYwlp
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ó bá ku ọjọ́ mẹ́ta sí Eré Ẹ̀yọ̀, ọmọ awo yóò ti wà ní Àwẹ̀ Adímú níbi ìpàdé, tí a ó ti ṣe Ìmòkù. #EyoOrisa #EyoFestival #Lagosat50
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aláké dárúkọ àwọn Aláṣẹ Igbákejì Òrìṣà ilẹ̀ wa lẹ́sẹẹsẹ bí ipò wọn ṣe tò tẹ̀lé 'ra. #YorubaBenin | #Yoruba #Benin #Oduduwa #Ogun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: NP: So Fun Won - @user #MusicHour cc @user"""""""" jẹ́ kí wọ́n mọ̀, kí wọ́n gbọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹṣeun o kò ní tán lápò o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nìkan jọmọ itan-akọọlẹ ti eré aṣikiri aṣikiri ti Andrew Dosunmu Iya ti George yoo ṣe diẹ sii lati ṣe afihan agbara fiimu naa, agbara ewi, o kere pupọ ni wiwo iyalẹnu.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ Kú ọjọ́ ìbí o @user. Ẹ ó gbòó. Ẹ ó tọ̀ ọ́. Ẹ ó f'ọwọ́ páwú, ferìgì jobì. Ẹ ò ní ráburú lọ́dún tuntun. Ire gbo gbo doríi yín. Àṣẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Sinima tó dára tòótọ́.. . . . Èyí gan-an ni sinima àgbéléwò aajo Nollywood tí ó dára jù tí mo ti wo. Ju gbogbo ẹ lọ, eka ijoba kan tó tayọ nǹkan Nollywood tẹ́lẹ̀. Àwọn onsere àti ààtò inú rẹ̀ rí idagbasoke àti òtítọ́. Noah àti Dominic ṣe dáadáa nínú ìṣeré wọn.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Episode 23| kọ́ ọmọ rẹ | Teach/Educate your children. On the program today is: 1. The Nigeria National anthem : """""""" orin orílẹ̀ èdè Nàíjírìa. 🎶 cc @user #yoruba #asa #ede https://t.co/ySWp3DtGE5
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ó jọ ọ́ àmọ́ kìí ṣe òun ni. Ìdí ni pé Àgùàlà jìnà sí wa gan-an kò sì bojú òrùn tán bí òṣùpá ṣe máa nbò ó.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: “@user: gbogbo nkan rere l'áíyé ni Ọlọ́run dá sí #Naija. Ó wá ku ìwà rere. Ìwà pẹ̀lẹ́.”Ati inu ire eniti konin ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ máa rọra ṣe o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
pẹ̀lẹ́ is to show empathy pity condolence àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bàbà ọkàa bàbà = millet bàbá = father baba = masterfather
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lọ ṣàwáríi gboard o ó lè fi àmì sí ọ̀rọ̀ ní orí ẹ̀rọọ̀ rẹ ire o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbìdánwò = attempt {ọ̀daràn gbìdánwò àti fo ìgànná ká tóó mú u - the criminal attempted jumping the fence before he was caught} #InYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àtọ̀sán latí ńpète òru ni wọ́n sọ olúwa má jẹ̀ẹ́ a rí ìyán ẹ̀ bá jẹ́ á pọnmi lẹ̀ de oǹgbe kí ebi má ba nà wá ńpàṣán
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ALÁÀFIN MÁKÙÚ Nígbà tí Aláàfin Adẹ́bọ̀ wàjà, Àrẹ̀mọ Mákùú gun orí ìtẹ́. Kí Aláàfin Mákùú tó jọba, Ọ̀yọ́ Mèsì ráńṣẹ́ sí Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfò Àfọ̀njá wípé, oṣù titun ti yọ ní Ọ̀yọ́. Ó ya Àfọ̀njá lẹ́nu wípé, kíákíá ni? Àfọ̀njá wí fún àwọn òjíṣẹ́ ààfin wípé,
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láàrin àwọn Yorùbá, bí wọ́n bá mú adìyẹ ìbílẹ̀ wá sí ilé láti sìn, wọ́n ma soó mọ́lẹ̀ fún ọjọ́ mélòó kan. Lẹ́hìn náà, wọ́n ma fi àyà adìyẹ náà wọ́lẹ̀ káàkiri ọgbà inú ilé. Ìdí ni wípé, kí ojú adìyẹ náà lè mọ ilé, kí ó sì jẹ̀ padà sílé, lẹ́hìn tí ó bá jẹ̀ lọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mọ àpadé-àti-àludé Ààtò Ẹgbẹ́ oríi Facebook Ẹgbẹ́ oríi Facebook ń mú ibi ìkẹ́gbẹ́, ìgbàwí àti àwọn ohun tí ó lágbára àti ààtò ẹgbẹ́ lè rí rúdurùdu.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ipade awon tibi............. https://t.co/vxXVM5H6pk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
10. Ẹsẹ̀ onígi ni àgéré,___ ni ìgèrè? A. Ẹsẹ̀ onírin B. Apẹ̀rẹ̀ tí a fi ń mú ẹja D. Eégún #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
awoorunmilaoselezo moforíbale oshaifá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
... Aa Fii Oro Yoo Oro ... Kii Jee, Kii Oro Oo Tan Booroo Booroo ...! #Yoruba #Proverb.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìkan lára àwọn eré alábala ilé Adúláwò tí ó dára jù.. . Ẹ̀bùn yẹn lé téńté. Ìșọwọ́ ṣeré àwọn ọmọbìnrin yẹn kún ojú òṣùwọ̀n. Bí wọ́n ṣe kọ eré náà kọ́ni lọ́gbọ́n wọ́n sì ríi ṣe.. . Nọ́líwuùdù, ẹ rí èyí ṣe, ẹ máa tẹ̀ síwájú.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ìgbà dodo ni àgbàdo ń gbani bí a kò pè é ní àgbàdo a lè pè é ní ìgbàdo bí a kò bá sì pè é ní àgbàdo tàbí ìgbàdo a ń
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e se ti e tele wa oh yoruba dun yungbayungba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àkújìn ẹni tí ó kú tí a sì fi gbogbo gbèsèe rẹ̀ jìnín mọ́remí ìrèmògún ìrèní ọmọ ògún ìrèé mògún ojúbọ ògún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♪ ... Àánú rẹ ló ṣe mi o, ló jẹ́ kí n bá ọ dámọràn, pé k'ó o bíbejì k'o tó bó'ra ♪ ~ Àyìnlá Ọmọwúrà. #Yoruba #music #Orin
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: 3. Orúkọ wo ni Yorùbá ń pe ẹranko inú àwòrán yìí? #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #Language https://t.co/QDPuV3Fd18
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fọ́nrán ẹ sọra fún àwọn wòlíì èké àti àwọn adamọdi olùṣọ́aguntan boo ṣàìsàn lọ sí ilé ìwòsàn bí ebi bá ń pá ọ ohun tí ó nílò ni owo tó múná doko tàbí isẹ gidi máa fi tọrọkobo tóo ni fún àwọn ọlọ́rọ̀ ló nínú àdúrà tààrà sọ́dọ̀ ọlọ́run
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣé b'ọ́dún ṣe ma lọ rè é, àwọn ọmọ wọ̀nyí ò mà tí í padàa tán àn? #BringBackOurGirls
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Bẹ́ẹ̀ ni. ó dára púpọ̀ fún kíkọ àwọn èrò ọkàn àti ìrírí ẹni sílẹ̀. Ẹṣé.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nínú Ifá Ẹlẹ́rìí Ìpín ni a ti bá ìtàn ohun t’ó fa sábàbí tí ẹyẹ oko fi di ẹyẹ ilé. #BiEyekoSeDiEyele #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pàṣán ni a fi ń na ẹlẹ́ṣẹ̀ mìíràn, a ó fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ ⛓️ dè é, a ó jáa lọ́rẹ́ gidi. #IdajoNileYoruba #Asa #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user shebi ale yii naa ni. Keshi o kede awon metadilogun ti o nlo fun idije naa a o ara ti o fee da
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Public Enlightenment in #Yoruba Language #Coronavirus Ifitonileti gbangba ni Ede Yoruba #COVID19N…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí erùpẹ̀ sahara òkun pupa òkun indian ni larubawa gbà orí òkun atlantic lòyìbó europe gbà wá ní tiwọn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìpápánu tí a fi gaàrí tútù tí a gbá jọ létí ajọ̀ bí a bá fẹ́ yan án ni a fi ń ṣe kàsádà a máa ṣù ú pọ̀ a ó fi iná yan án bíi àkàrà búrẹ́dì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Oloore l'ore ńwọ́ tọ̀. (Kindness follows the kind-hearted.) #yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìsekúse gbàá
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ewé ńlá mi ò ní rún wẹ́wẹ́, òkè ńlá ò ní di òkìtì-ọ̀gán. Gíga gíga là á b'ọ́jọ́. gíga là á b'óṣù. Ewé ńlá ni tèmi, ewé ìrókò ewé aládé, ewé ọlọ́pẹ ewé olóye, ewé wọ́rọ̀ lálẹ́ odò. Orí dákun dábọ̀ máà dá mi padà sẹ́yìn, ewé ńlá ni kí o ṣe mí. #Iwure #Yoruba #OjoAje
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: D'banj Ti Fe Le Gaari Ijebu Wole Pelu Koko Garri: D'banj ti se ifilole Garri re eleyii to pe ni 'Koko Garri'. ... http://t.co/g…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò Sí bí òkèlè ṣe lè lọ lọ́fun bí a lo ṣíbí, kò le dùn. @user @user @user @user #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọba sàláùdéèn òyèfùsì ọmọ aṣàlè jẹ̀jẹ̀ bí ẹni tí ò róbìnrin rí tó papòdà bí o dé alákeji ìsálú kí o kí bàbáa mi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Ẹ ẹ̀ rí mi kọ́? Alátiṣe ní í màtiṣe ara rẹ̀ o :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user “Gomina ana ni ipinle kwara Sen Bukola Saraki nje wo esun bi o se nawo ipinle na bayi, alaye…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àyájọ́ òní ọdún ni a bí olóògbé ọ̀kọrin àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ọmọènìyàn nì olúfẹlá aníkúlápò kútì h
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ìlagbà ni ọ̀rọ̀ rẹ́ gbà, ó kọjá ìṣán. Ó yá lọ wò ó wá! Àfira!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀yin tí ẹ ò ṣòpò gbìyànjú iyè ti yín náà ò ní ra o yóò máa lékún síi ni lágbára ọba amòye
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orílè̟èdè náà ìbáà wà ní òmìnira tàbí kí ó wà lábé̟ ìs̟àkóso ilè̟ mìíràn wo̟n ìbáà má dàá ìjo̟ba ara wo̟n s̟e tàbí kí wó̟n wà lábé̟ ìkánilápákò yòówù tí ìbáà fé̟ dí òmìnira wo̟n ló̟wó̟ gé̟gé̟ bí orílè̟èdè
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #TweetinYoruba oruko mi ni Hassan Adebayo, Akanbi omo Jagun, omo Ago Ishona, ni ilu Oyo Alaafin. E kaaro. Aku ola Jimoh…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ọ̀tun-ọ̀tun lọjọ́ ń yọ. N óò máa bọ́jọ́ ta. #Ekaaro http://t.co/TNSumTpG57
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
adetola ni oruko mi abi mi si ebutemetta isaleeko ni agbe bi baba mi ebutemetta ni agbe bi iya mi omo igbomina ni mi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀gbómọ̀ṣọ́, Kakanfò àti Ẹdun Gbógun, fi iṣẹ́ kan náà kàn sí Olówu ti Òwu. Bí Olówu Ti Òwu tí ń jẹ́ iṣẹ́ wọ̀nyìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ni ó parun. Ìkòyí Igbó, Apòmù, Ìkirè, Iràn, Ìsẹ́yìn, Gbàngán àti àwọn ìlú òmíràn bẹ́ẹ̀, ni Òwu parun. Àwọn ikú wọ̀nyìí wà ní
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ibi abẹ́rẹ́ bá fi ojú ọ̀nà sí, òhun lokùn ńtọ̀. / It's wherever the needle identifies as the way, that the thread f ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: Ọba t'ó jẹ tí ìlú tòrò ... #Nigeria #GEJ""""""""Oruko koni pare ninu iwe itan.LaiyeLaiye.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
láàfin kẹ̀dẹ̀ré níṣe nìlùu gbẹ̀du yóò máa fọhùn pé ọba ti fayé sílẹ̀ lo dara pọ̀ mọ́n àwọn irúnmọlẹ̀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
B. Ìgèrè ni apẹ̀rẹ̀ tí a fi ń mú ẹja lódò. Ó yàtọ̀ sí àwọ̀n. https://t.co/V5kW5HX73O
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ododo oro. Ibukun oluwa lo ng muni laa laise laa laa""""""""""""""""@user: Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ o. Kìràkìtà ò dọlà.""""""""""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
olùdíje fún ipò ààrẹ orílẹ̀èdè ùgándà bobi wine |
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọlọ́jọ́ Òní ò! Bí ojú ọjọ́ yìí bá lè gb'ójú dúró báyìí, kì bá dáa. Ara tun 'ni pẹ̀sẹ̀!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Bíbí ire kò ṣé fowó rà. Ẹkú ọjọ́ ìbí o. Ẹ̀mí á ṣọ̀pọ̀ rẹ̀ láíyé. Ọdọdún lá nrí ọmọ obì lórí àtẹ. Ire lẹ́ ó máa rí títí aiyé!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
20, 000 likes. E se gan o. Apapo omo Yoruba.🍉🥰🍉🥰🥰🔥👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi… https://t.co/wfEqy7zT8j
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e ò gba gbìyànjú síi ọ́ ni kò kí n ṣe o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ ìyá mi ọmọ kílóńṣẹlẹ̀ ń kọ́ níbẹ̀ bá mi kii o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àmójúkúrò ni í mú ẹ̀mí ìfẹ́ gùn willingness to overlook is what makes loving relationships endure be tolerant no
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Reposted from @user - Èdè Yorùbá L'árinrin l'órí Rédíò @user pẹ̀lú @user moninkanola @user @user E maa gbo Tele wa 👉@user #edelman #ede #yoruba… https://t.co/KhvfM30aDt
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yorùbá l'aó fi s'àlàyé gbogbo oun t'ó bá n'selè ní gbogbo àgbáye l'òní... #TweetInYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Baba wa ṣe bí Ajẹ́ẹ̀rí Jèhófà rí nígbàanì kí ohun gbogbo tó daríkodò, kí a tó máa fi ojú egbò gúnlẹ̀. #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user """"""""Ó ti tó, mi ò fẹ́ bẹ́ẹ̀ mọ́"""""""" Ṣé ẹni tí kò gbọ́ Yorùbá ló kọ Yorùbá dáadáa báyìí? :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo ohun bá gba àyè, tí ó wúwo; tí a lè fi ọwọ́ kan ni #Matter | #Science
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àyé yi o lé, àwà òmò ēniyàn lò sò ìlē àyē dī ōgùn! #Yórúbà proverb. https://t.co/axkn9CUClJ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
onise iyanumiracle worker onise arawonderful onise nlagreat god mimo mimo mimoholy holy holy oba to ninu mi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oke oke lemu ru siko si aseti fun omo olorun lọ́jọ́ òní ijó àjólọsíwájú ni a ò ní jó àjórẹ̀hìn lágbára
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user se ekun ni ogidan abi kiniun?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#SMWHQ ni mo wà lónìí fún #SMWLAGOS. Ta ló ń bọ̀? #smwl55forward @user @user :) http://t.co/i3RfuqeEj7
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train