raw_text
stringlengths
2
128k
hiroki fujiharu hiroki fujiharu bi november 28 1988 je a japanese bọọlu player ti o yoo bi a osi ni kikun-pada fun gamba osaka ni j league division 1
julianne moore julianne moore je osere to gba ebun akademi bi obinrin osere todarajulo
jennifer lawrence jennifer shrader lawrence je osere to gba ebun akademi bi obinrin osere todarajulo
matthew mcconaughey matthew mcconaughey je osere to gba ebun akademi fún osere okunrin didarajulo
eddie redmayne eddie redmayne je osere to gba ebun akademi fún osere okunrin didarajulo
leonardo dicaprio leonardo wilhelm dicaprio je osere to gba ebun akademi fún osere okunrin didarajulo
brad pitt brad pitt jẹ́ òṣèré eré orí ìtàgé àti atọ́kùn eré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti gba ẹ̀bùn akádẹ́mì lẹ́ẹ̀mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí olùgbéjáde eré lábẹ́ ilé iṣẹ́rẹ̀ plan b entertainment pitt kọ̣́kọ́ di mímọ̀ gẹ́gẹ́ bíi darandaran nínú eré thelma louise 1991
elisha cuthbert elisha ann cuthbert phaneuf november 30 1982 je osere ara canadian
m c gainey michael connor m c gainey january 18 1948 je osere ara amerika
ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀ ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀ tí a mọ̀ láti ìṣẹ̀wá sí yẹ́lò jaki tàbí àjálù pupa jẹ líle àkóràn àrùn ní ọ̀pọ̀ ìṣẹlẹ̀ lára aamì ni ibà òtútù àìle jẹun èébì iṣan dídùn pàápáà ní ẹhìn àti orí fífọ́ àwọn aamì sábà maa ń jẹyọ láàrín ọjọ́ márùn ùn àwọn ènìyàn kan láàrín ọjọ́ kan tí ara wọṅ ti ń dá ìbà náà padà wá inú...
garry shandling garry emmanuel shandling november 29 1949 march 24 2016 je osere ara amerika
drew massey drew massey je osere ara amerika
valparaíso valparaiso ni a pataki ilu kansoso ati eko ile-ni county tabi commune ti valparaiso chile o tobi valparaiso ni keji tobi agbegbe metropoli ni orile-ede
àjẹsára ibà jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ a àjẹsára ibà jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ a jẹ́ àjẹsára tó má a n dènà ibà jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ a a má a ṣiṣẹ́ lára iye àwọn ènìyàn tó fẹ́rẹ̀ tó 95 nínú àwọn tó gbàá agbára rẹ̀ a sì má a wà fún ìgbà tó tó ó kéré jù ọdún mẹ́ẹ̀dógún tó bá sì ṣeé ṣe jálẹ̀ ìgbé-ayé ènìyàn bí a bá fifúnni ìwọ̀n egbògi náà méjì ni a dámọ̀r...
àjẹsára àrùn ìta àjẹsára àrùn ìta jẹ́ àjẹsára tó ní agbára púpọ̀ láti dènà àrùn ìta lẹ́yìn ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo iye àwọn ọmọ oṣù mẹ́ẹ̀sán tó pọ̀ tó 85 àti àwọn ọmọ tó ti ju oṣù méjìlá lọ tó pọ̀ tó 95 ni yóò ní agbára tó péye láti kojú àrùn náà ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ gbogbo àwọn tí kò ní agbára àti kojú àrùn náà lẹ́yìn tí wọ́...
hugh hefner hugo marston hugh hefner 1926-2017 je osere ara amerika
ed o'neill edward leonard ed o'neill april 12 1946 je osere ara amerika
hms birkenhead hms birkenhead ke skepe sa brittania ya 1845
michael jeter michael jeter august 26 1952 march 30 2003 je osere ara amerika
àwọn àjẹsára hpv àwọn àjẹsára kòkòrò ara wíwú ènìyàn hpv jẹ́ àjẹsára tí ó maa ń dẹ́kun àkóràn ti àwọn irúfẹ́ kòkòrò ara wíwú ènìyàn àwọn àjẹsára tí ó wà ń dábòbò lòdì sí àwọn irúfẹ́ bóyá méjì mẹ́rin tàbí mẹ́sàn ti hpv gbogbo àjẹsára ni o ń dábòbò ó kéré hpv 16 ati 18 tí ó ń ṣòkunfa ewu kòkòrò jẹjẹrẹ abẹ́ obìnrin tí ó l...
ian mcshane ian david mcshane september 29 1942 je osere ara ilẹ̀ọba aṣọ̀kan
mick wingert mick wingert july 4 1974 je osere ara amerika
greg kinnear gregory buck greg kinnear june 17 1963 je osere ara amerika
doris roberts doris may green november 4 1925 april 17 2016 je osere ara amerika
glenn close glenn close march 19 1947 je osere ara amerika
moscow international business center moscow international business center rọ́síà wọ́n tún ń pèé ní moscow-city rọ́síà jẹ́ agbèègbè ìṣòwò ní àárín moscow russia
don rickles donald jay don rickles may 8 1926 april 6 2017 je osere ara amerika
steve harvey broderick stephen steve harvey january 17 1957 je osere ara amerika
àjẹsára ibà jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b
àjẹsára dídáranjẹ̀ ọpọlọ ti japaníìsì àjẹsára dídáranjẹ̀ ọpọlọ ti japaníìsì jẹ́ àjẹsára tí ń dáàbò bo ni lọ́wọ́ dídáranjẹ̀ ọpọlọ ti japaníìsì ìwọ̀n agbára àwọn àjẹsára náà láti ṣiṣẹ́ ju bíi 90 lọ iye àsìkò tí ààbò egbògi náà fi ń wà lára kò tíì fi bẹ́ẹ̀ ye ni dáradára ṣùgbọ́n agbára iṣẹ́ rẹ̀ dàbí èyí tó má a ń dínkù bí...
àjẹsára rotavirus àjẹsára rotavirus jẹ́ àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí à ń pè ní rotavirus àwọn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn wọ̀nyí ló má a ń sábà ṣe òkùnfà ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ láàárín àwọn ọmọdé àjẹsára náà a má a dènà ìwọ̀n 15 sí 34 ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru tó lág...
simi simísolá bọlátitó kosoko listen tí a bí ní ọjọ́ mókàndínlógún oṣù kẹrin ọdún 1988 tí a mọ̀ sí simi jẹ́ olórin akọrin àti òṣèré nàìjíríà ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọrin ihinrere tí ó sì tú àwo orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde ní 2008 tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ ogaju ó tún ṣeré bí ọ̀kan nínú àwọn adájọ́ gíga jùlọ ní àkókò 7 tí ìfih...
peter kelamis peter kelamis december 11 1967 je osere ara amerika
àjẹsára táífọ́ọ̀dù àjẹsára táífọ́ọ̀dù jẹ́ àjẹsára tí n dènà ibà táífọ́ọ̀dù oríṣi méjì ni ó wà káàkiri ty21a tó jẹ́ àjẹsára tó wà láàyè tí a sì má a n gba ẹnu fúnni àti àjẹsára vi capsular polysaccharide èyí tó jẹ́ abẹ́rẹ́ àjẹsára ẹlẹ́yọ ìwọ̀n agbára wọn tó 30 sí 80 fún bí ọdún mẹta àjọ ìlera àgbáyé who gbani nímọ̀ràn p...
lorne cardinal lorne cardinal january 6 1964 je osere ara amerika
jim carrey james eugene jim carrey ọjọ́ mẹ́tàdínlógún oṣù kínnín ọdún 1962 jẹ́ òṣèré aláwàdà olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀ èdè àmẹ́ríkà àti canada
jason alexander jay scott greenspan september 23 1959 je osere ara amerika
alan zweibel alan zweibel may 20 1950 je osere ara amerika
mike adenuga michael adeniyi agbolade ishola adenuga ojoibi 29 april ọdún 1953 jẹ́ oníṣówó àji olùdásĺlẹ ilé-iṣẹ globacom adenuga jẹ́ ìkan lára ọmọ orílẹ ède nàìjíría tí ó lówó jùlọ ó di olówó lati ibi òwo nẹ́ tíwọki `ẹrọ alágbéka àti epoor`ọbì
rajinikanth shivaji rao gaekwad bìi ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejìlá ọdún 1950 wọ́n t́n mọ̀ọ́ sí rajinikanth jẹ́ òṣère eré ìtàgé orílẹ èdè indian tí ó ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ fiimu tamil ó ti kópa nínú eré àwon bollywood telugu kannada malayalam hollywood ati eré ìtàgé ní ède bengali ó b`ẹr`ẹ eré ìtàgé ṣíṣe nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ olù...
àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b jẹ́ àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b ọmọ tuntun a maa gba àkọ́kọ́ abẹ́rẹ́ àjẹsára yíi láàrín wákàtí mẹ́rìndínlógún tí wọ́n bíi àti abẹ́rẹ́ yíi méjì tàbí méta lẹ́yìn ìgbà náà èyí pẹ̀lú àwon tí ara wọn kò ní anfààní púp...
world health organization
hepatitis c
springbok springbok jẹ́ alábọ́dé ẹtu tí wọ́n ń rí ní gúúsù áfríkà àti gúúsù-wọ̀orùn áfríkà ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ antidorcas jẹ́mánì onímọ̀ ẹranko eberhard august wilhelm von zimmermann ló kọ́kọ́ ṣe àpèjuwe ọmọ ẹbí bovidae yìí ní ọdún 1780 ẹ̀yà méta ẹranko yìí tí di mímọ̀ ẹtu èyí tẹ́ẹ́rẹ́ tẹ́sẹrẹ̀ gùn springbok gùn...
kola oyewo kola oyewo bìi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọn oṣù kẹta 1946 jẹ́ òṣèré àti olùkọ́ ọmọ orìlé èdè nàìjírìà ìgbà èwe a bìi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọn oṣù kẹta 1946 ní ìlú ọ̀bà ilé ti ìlú ọ̀ṣun gúúsù-wọ̀orùn nàìjírìà ètò ẹ̀kọ́ ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti obáfẹ́mi awólọ́wọ̀ yunifásitì níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí nínu ìmo eré ìt...
ola rotimi ọláwálé gladstone emmanuel rótìmí tí a mọ̀ sí olú rótìmí 13 oṣù kẹrin 1938 18 oṣù kẹjọ 2000 jẹ́ ògbóńta olùkọ̀tàn ọmọ orìlé èdè nàìjírìà àti olùdarí tíátà wọn a má pèé ní okùnrin oní tíátà tí kò lábàwọń òṣèré olùdarí onijo kòríógíráfì àti oníṣẹ́-ọnà tí ó ṣe àyè iṣẹ́ tí ọnà kópa ní ìgbésí ayé rẹ̀ola rotimi ni...
saworoide saworoide jẹ́ eré àgbéléwò tí tunde kelani darí àti tí mainframe films àti television production ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 1999 àkójọ saworoide ṣe àfihàn ètò àṣà yorùbá pípẹ́ kan ní ìlú jogbo níbi tí èèyàn kò lè jẹ oba láìjé pé èèyàn tó tọ́ lú ìlu saworoide
daisy ducati daisy ducati ojoibi oṣù kejìlá 8 1989 je omo áfríkà amẹ́ríkà osere ara àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà
colin howell colin howell bi ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹta ọdún 1959 jẹ́ northern irish tí a gbé si ẹ̀wọ̀n fún ẹ́sún apànìyàn àwon apànìyàn áti ìròyìn tì o yíi wọn ká jẹ́ fífi hàn lóri itv eré onípele the secret gbóhùnsáféfé ní oṣù kẹrin àti oṣù karun ọdún 2016 howell pa aya rẹ̀ lesley née clarke àti olólùfé ọkọ rẹ́ trevor buc...
australopithecines australopithecines jẹ́ orúkọ tí à ń pe àwọn ẹ̀ya ẹranko tí ó jẹ mọ́ australopithecus àti paranthropus àti àwọn tí ó fẹ́ jẹ mọ́ ẹgbẹ́ kenyathropus ardipithecus àti praeanthropus
list of human evolution fossils àwọn tábìlì yíi ṣe àlàyé ránpẹ́ nípa àwọń hominin mímọ̀ tàtijọ́ tí o jẹ mọ́ ìdá ènìyàn lati ìbèère ìdá homini di ikẹyìn miocene bí ọdún mílíọ́nù mẹ́fà sẹ́yìn àkàsíwájú http//booksgooglecom/id=ezm1oa_s6iscprintsec=frontcoverdq=hartwig+primatecd=1#v=onepageqf=false 1994 the cambridge encyc...
john leguizamo jonathan alberto john leguizamo ọjó kejìlélógún oṣù keje ọdún 1964 jẹ́ òṣèré ará améríkà
àjẹsára meningococcal àjẹsára meningococcal jẹ́ èyíkèyí àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí à ń pè ní neisseria meningitidis oriṣiriṣi ẹ̀yá àjẹsára yìí lo ń ṣiṣé fún díẹ̀ nínú tàbí gbogbo oriṣi meningococcus a cw135 àti y ó kéré jù àjẹsára yìí ń ṣiṣé dáadáa láàrín 85 sí 100...
àjẹsára rubella àjẹsára rubella jẹ́ àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí ti o n fa àìsàn kan tí à ń pè ní rubella iṣẹ́ tó múná dóko rẹ̀ ma ń bẹ̀ẹ̀rẹ̀ lẹ́yìn ọsẹ̀ méjì tí a bá gba abẹ́rẹ́ àjẹsára yìí àti pe ́ bíi aarundinlogorun 95 máa ní ìí jẹsára yìí orílẹ̀ èdè tí ó ní àjẹsára yìí púpọ̀ k...
surulere surulere jẹ́ ibùgbé àti ibi iṣòwò agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní òke-odò ní ìlú èkó ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà agbègbè yíi tó ìwọn 23 km² ìkànìyàn tí wọ́n ṣe ní ọdún 2006 fihàn wípé ó kéré jù ènìyàn 503975 ń gbé agbègbè yìi pẹ̀lú ìṣúpọ̀ olùgbé bíi 21864 fún ìdá kan km² àkópọ̀ ibẹ̀ ni pápá ìdárayá ti ...
william harper olóṣèlú ilẹ̀ rhodesia william john harper ọjó kejìlélógún oṣù keje ọdún 1916 ọjó kẹjọ oṣù kọkànlá jẹ́ olóṣèlú agbaṣẹ́ ṣisẹ́ àtí awakọ̀ òfúrufú ológun royal air force tí ó jẹ́ ìránṣẹ́ óṣèlú ilẹ̀ rhodesia láti ọdún 1962 sí 1968 tí ó tọwọ́ bọ ìwé tí ìlú náà fí gba òmìnira lati ọwọ́ gẹ̀ẹ́sì ní ọdún 1965 wọ́n...
ẹ̀bùn akádẹ́mì
ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù
àjẹsára igbọ́n amú ọpọlọ wú àjẹsára igbọ́n amú ọpọlọ wú jẹ́ àjẹsára tí a ńlò láti dẹ́kun igbọ́n amú ọpọlọ wútbe àrùn yíì wọ́pọ̀ ní àarín àti ìlà-oorùn úròpù àti àriwá éṣíà ju ìdá 87 àwọn ènìyàn tí ó gba àjẹsára ni kòní ààrùn ó wúlò nígbà tí igbọ́n tí ó ní ààrùn bágé ènìyàn jẹ a máa ń fún ènìyàn nípa fífún ènìyàn ní abẹ...
will poulter william jack will poulter bíi ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kínín ọduń 1993 jẹ́ òṣèré gẹ̀ẹ́sì òhun ni gally nínú eré tí ó ṣàmúbádọ́gba ìwé ìtàn ọ̀dọ́mọkùnrin kan tí ó bá ara rẹ̀ ní àwùjọ tí kódáranínú nínú eré the maze runner ní ọdún 2014 tí ó sì gbà ẹ̀bùn bafta rising star òhun ní lee carter nínú eré son of ra...
joigny coach crash joigny coach crash jẹ́ ìjàmbá ọkọ̀ kan tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọ̀nà ọkọ̀ a6 ní joigny yonne orílẹ̀ èdè fránsì ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹfà odún 1990 nígbà tí ọkọ̀ gẹ̀ẹ́sì double-decker tó lámì kọlù nkan ní ìgbìyànju lati ṣe ìfipáju àkókò tó ti ṣòfò ó wa ọkọ́ tí ó ń sáré rin máìlì méjìdínlọ́gọrin ní wákàtí kan 126km/h...
ìfipá gba maersk alabama ìfipá gba maersk alabama jẹ́ àtẹ̀léra ìṣẹ̀lẹ̀ orí omi tì ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ajalèlókun merin tí wọ́n fi ipá gba ọkọ̀ ojú omi ẹ̀lẹ́rù mv maersk alabama ogòjílénírinwó máìlí 440 km 280 mi gúúsù-ìlàoòrùn eyl somalia ìdíwọ́ yìí parí lẹ̀yin akitiyan ológun ojú omi us lati gbàwọn sílẹ̀ ó jẹ́ àkọkọ́ ...
mohammed bin zaal mohammed zaal jẹ́ onísòwò láti uae tì ò dà ilè-isẹ̀ kìkọ̀ sìlẹ̀́ nì dubai bì á́wọn elèyi the reserve the nest seventh heaven and ashjar mohammed zaal wà nì àkójọpọ̀ làti ọwọ́ arabian business ninu ọgọ́run alágbára jùlọ lárúbáwá lábẹ́ ogójì àti nípa scoop empire nínu méjì-lélógún alágbára jùlọ̣ emirati...
ìfipá gba maersk alabama ìfipá gba maersk alabama jẹ́ àtẹ̀léra ìṣẹ̀lẹ̀ orí omi tì ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ajalèlókun mẹrin tí wọ́n fi ipá gba ọkọ̀ ojú omi ẹ̀lẹ́rù mv maersk alabama igbalélógójì máìlí 440 km 280 mi gúúsù-ìlàoòrùn eyl somalia ìdíwọ́ yìí parí lẹ̀yin akitiyan ológun ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà la...
ìfipá pa gba maersk alabama
ológun ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà ológun ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà jẹ́ ẹ̀ka iṣẹ́ ogun tí ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà àti pé ó jẹ́ ìkan nínú meje aláṣọ ogun fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà ológun ojú omi fún àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà jẹ́ èyí tọ tọbi jù tí ó sì pójuwọ̀n ...
ológun ojú omi united states
ogun barbary kejì ogun barbary kejì 1815 - 1816 jẹ́ ogun kejí nínú ogun méjì tí ó ṣélẹ́̀ láàrin àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà àti ottoman empire tí àríwá àfíríkà tí ó jẹ́ adelé fún tripoli tunisia àti algeria
captain phillips eré captain phillips jẹ́ eré amẹ́ríkà aṣaragágá ọdún 2013 tí paul greengrass darí ti tom hanks àti barkhad abdi kópa tí ó da lórí ìgbésíayé ẹnìkan tí ó yè eré yìí dá lórí ìtan ìfipá gba maersk alabama tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2009 ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí àwọn ajalèlókun ti òkun india tí adarí wọn jẹ́ abd...
ìjalèlókun ìjalèlókun jẹ́ ìwa olèjíjà tàbí ìwà ọ̀daràn ní okun àwọn tí ó ń lọ́wọ́sí ìwà ìjalèlókun ni wọ́n ń pè ní àwọn ajalèlókun àkosílẹ̀ àpẹẹrẹ ìjalèlókun tí ó pẹ́jù ṣẹlẹ̀ ní bíi orundún mẹ́rìnlá sẹ́yìn nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ ajalè lórí òkun dojú kọ ọkọ̀ ojú omi ti aegean àti mediterranean tí kò digun àwọn ònà tóóró tí...
juyik juyik persian جوئيک‎‎ jẹ́ jūyīk ní èdè latini a tún lépè ní jūyīg jẹ́ abúlé ní agbèègbè bahu kalat agbèègbè dashtiari sistan àti ìgbèríko baluchestan ìránì ní ìkànìyàn ọdún 2006 gbogbo ènìyaǹ tó ń gbé ní abúlé yìí jẹ́ igba àti mẹtàléláàdọ̀rín nínú ẹbí mẹ́rìndínláàdóta
agbèègbè ìdìbò ti paddington queensland agbèègbè ìdìbò ti paddington jẹ́ tí àwọn tí ó lẹ̀tọ́ làti dìbò fún aṣojú ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ti ìpínlẹ̀ queensland australia ìtàn wọ́n dá paddington sílẹ̀ ní ọdún 1911 lẹ́yìn àtúnpín ìlú tí o sẹlẹ̀ ní ọdún 1912 nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ agbèègbè ìdìbò yí wà títí dì ọdún 1932 ní àkókò ìdì...
richard phillips oníṣòwò ojú omi richard phillips bíi ọjó kẹrindínlógún oṣù karún ọdún 1955 jẹ́ oníṣòwò ojú omí ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà tí ó jẹ́ ògá ọkọ̀ mv maersk alabama nígbà tí àwọn ajalèlókun tí somalia fẹ́ já ọkọ̀ náà gbà ní oṣù kẹrin ọdún 2009 ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí phillips ní massachusetts ó kàwé jade ní ilé ìwé...
electoral district of paddington queensland
david kaufman david kaufman july 23 1961 je osere ara amerika
miyamoto musashi miyamoto musashi 1584 - ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 1645 jẹ́ àwọn olùkọ̀wé ronin samurai àti olórin
jan joosten van lodensteijn jan joosten van lodensteijn 1556 1623 jẹ́ atukọ̀ ará ilé ọba àwọn nẹ́dálándì
mv maersk andaman mv maersk andaman tẹ́lẹ̀tẹ́lè maersk alabama jẹ́ ọkọ̀ ojú omi ẹlẹ́rù ti maersk line limited tí ó wà ní ìmú ṣiṣẹ́ waterman steamship corporation ó ní àwọ̀ búlu tí ó fẹ́ mọ́ díẹ̀ pẹ̀lú ìrísí bi ti ọkọ̀ maersk tókù láì wo tí àsíá ìforúkọsílẹ̀ wọn àwọn ajalèlókun jáagbà lẹgbẹ́ somalia ní ọdún 2009 wọ́ sí ...
moscow city
ilẹ̀ọba àwọn nẹ́dálándì
michael j fox michael andrew fox june 9 1961 je osere ara amerika
nasir ol molk mosque nasir ol molk mosque persian مسجد نصیر الملک masjed e nasir ol molk‎‎ tí wọ́n tún mọ̀ sí mọ́ṣáláṣí aláwọ̀ pupa fẹ́ẹ́rẹ́ jẹ́ mọ́ṣáláṣí ìbílẹ̀ ní shiraz iran ó wà ní agbèègbè gowad-e-arabān nítòsí šāh čerāq mosque mọ́ṣáláṣí yìí ní gílásì aláwọ̀ àràbarà tí ó sí ṣe àfihàn àwọn èròjà ìbílẹ̀ bíi panj kās...
paul petersen william paul petersen september 23 1945 je osere ara amerika
nils olav colonel-in-chief sir nils olav jẹ́ ọba penguin tí ó ń gbé ní edinburgh zoo scotland ó jẹ́ ẹran ọ̀sìn fún ológun tí wọ́n máa ń lò nígbà ayẹyẹ tàbí gẹ́gẹ́ bí ààmi àpẹẹrẹ tí ó sì jẹ́ ọ̀gágún colonel fun royal guard ti orílẹ̀ èdè norway àwọn ológun lati norwegian royal guard bẹ nils wò ní ọjọ́ karùndílógún oṣù kẹ...
edinburgh zoo edinburgh zoo tẹ́lẹ̀tẹ́lè scottish national zoological park jẹ́ ọgbà ẹranko fun ìdárayá 82-acre 33 ha kan tí kò sí fún èrè tí ó wà ní olúìlú scotland wọ́n kọ́ọ ń ọdún 1913 tí ó sì jẹ́ pé royal zoological society of scotland lónii ó máa ń gba èrò tí ó ju 600000 lọ́dọọdún tí ó sì jẹ́ kí ó jẹ́ ìkejì ibi tí ó...
george tucker olóṣèlú george tucker ọjọ́ ogún oṣù kẹjọ ọdún 1775 ọjọ́ kẹwá oṣù kẹrin ọdún 1861 jẹ́ amòfin ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà oléṣèlú olùkọ̀tàn olùkọ̀wé àti olùkọ́ni ara àwọn iṣẹ́ mọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà ni àkọ́kọ́ ìṣẹ̀tàn ayé amúnisìn ní virginia àti àwọn míràn nínú iṣẹ́ àkọ́kọ́ ìṣẹ̀tàn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ tí orílẹ̀ èdè yìí tucke...
thomas haden church thomas richard mcmillen june 17 1960 je osere ara amerika
tick-borne encephalitis vaccine àjẹsára igbọ́n amú ọpọlọ wújẹ́àjẹsára tí a ńlò láti dẹ́kun igbọ́n amú ọpọlọ wútbe àrùn yíì wọ́pọ̀ ní àarín àti ìlà-oorùn úròpù àti àriwá éṣíà ju ìdá 87 àwọn ènìyàn tí ó gba àjẹsára ni kòní ààrùn ó wúlò nígbà tí igbọ́n tí ó ní ààrùn bágé ènìyàn jẹ a máa ń fún ènìyàn nípa fífún ènìyàn ní a...
pneumococcal vaccine àjẹsára ìlòdìsí kòkòrò inú jẹ́ àjẹsára alòdìsí kòkòrò ìlò wọn lè dẹ́kun àwọn irúfẹ́ àrùn ẹ̀dọ̀fóró àrùn wíwú ọpọlọ tàbi ́egungun ẹhìn àti àrùn ìṣàkóbára ara-ẹni irúfẹ́ àjẹsára ìlòdìsí kòkòrò inú méjì lówà àjẹsára àjùmọ̀ṣe àti àjẹsára ọ̀pọ̀ ṣúgà wọ́n maa ń fúnni bóyá nípa abẹ́rẹ́ ninú iṣan tàbí lábẹ...
ilé alàgbà nàìjíríà
baselios cleemis baselios cleemis thottunkal malayalam ബസേലിയോസ് കർദ്ദിനാൾ ക്ലിമ്മീസ് tàbí tí wọ́n bá fẹ́ gẹ́gẹ́ bí olórí ecclesiastical baselios cleemis cardinal thottunkal jẹ́ major archbishop ti syro-malankara catholic church pope benedict xvi yànhán sí college of cardinals tí catholic church ní papal basilica of sa...
montenẹ́grò
venus and adonis veronese madrid venus and adonis jẹ́ àwòrán kíkùn tí olóògbé paolo veronese ayàwòrán ọmọ orílẹ̀ èdè italy yà ní ọdún 1580 tí ó wà ní museo del prado ní madrid báỳí wọ́n fẹ àwòrán ti tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ lọ́wọ́ òkè ní ọrundún méjìdínlógún sẹ́yìn wọ́n yọ abala èyí tí wọ́n fi kun kúrò lati dáapadà c 1988 kí iṣẹ́ ...
professor peller professor moshood abiola peller tí wọ́n bí ọdún 1941 ní ìséyìn ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1997 onípànù jẹ́ onídán orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti ọkàn lára àwọn ògbóǹtarìgì onídán ní ilẹ̀ áfíríkà orúkọ bíbí rẹ̀ jẹ́ fọlọ́runshọ abíọ́lá peller lọ sí ilé-ìwé mùsùlùmí ní ìséyìn àti ilé-ìwé native authority primary...
sístẹ̀mù ìṣiṣẹ́ kọ̀mpútà
biochemistry <noinclude> biochemistry nígbàmíràn wọ́n máa ń pèé ní biological chemistry jẹ́ ìmọ̀ ìlànà kẹ́míkà àgọ́ ara àtí ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú ohun ẹlẹmí nípa ṣíṣe àkóso lílọ-bíbọ̀ iṣẹ́ lágọ́ ara nípasẹ̀ ìtalólobo ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà àti lílọ-bíbọ̀ agbára kẹ́míkà làtàrí gbogbo ìbáṣepọ̀ kẹ́míka nínú ara ìlànà kẹ́míkà nínú ...
àkójọ àwọn olórí ẹgbẹ́ ò ṣèlú communist party of china communist party of china jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú people's republic of china prc èyí ni àkójọ àwọn olórí ẹgbẹ́ òṣèlú communist party of china
len deighton bibliography len deighton bíi ọjọ́ kejídínlógún oṣù kejí ọdún 1929 jẹ́ olùkọ̀tàn gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n mọ̀ sí àwọn ìwé àkàkọ́gbọ́n àwọn iṣẹ́ ìtàn ológun ìfàwòránsọ̀tàn àtí kíkọ nípa bí a ṣe ń se oúnjẹ́ ó ní oríṣiriṣi iṣẹ́ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú àkàra díndín agbáwo oúnjẹ ara àwọn olùkọ̀wé ìròyín olùkọ́ àti ara àwọn to ń ...
matt k miller matthew kermit miller bíi ọjọ́ kejì oṣù kejì 1960 jẹ́ olùkọ̀tàn òṣèré àti aláwàdà ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà wọ́n tún mọ̀ó sí kermit miller àti kermit beachwood
john goodman jonathan stephen john goodman bíi ọjọ́ ogún oṣù kẹfà ọdún 1952 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà