raw_text
stringlengths
2
128k
ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
ibi ìwòràwọ̀ lati vienna ibi ìwòràwọ̀ lati vienna jẹ́ ibi tí wọ́n ti ń wòràwọ̀ lati orílẹ̀ èdè vienna ní austria ó jẹ́ ara university of vienna wọ́n kọ́ ibi ìwòràwọ̀ àkọ́kọ́ ní ọdún 1753 sí 1754 lórí òrùlé ìkan lára àwọn ilé tó wà ní yunifásitì yìí tí emperor franz joseph i of austria pàṣẹ iṣàmúlò rẹ̀ ní ọdún 1883 yàrá...
ìwòràwọ̀ lati vienna
mike pollock michael b mike pollock march 9 1965 je osere ara amerika
microlophus albemarlensis alángba àpáta galápagos microlophus albemarlensis tí wọ́n tún mọ̀ sí alángba àpáta albemarle jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù galápagos níbi tí ó ti wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù ìwọ̀ oòrùn archipelago àwọn erékùṣù ńlá isabela santa cruz fernandina santiago àti santa fe àti àwọn ọ̀pọ̀l...
microlophus microlophus jẹ́ ti ìdílé àwọn alángbá tropidurid ní gúúsù amẹ́ríkà ogún ẹ̀yà alángbá yìí ni a dámọ̀ tí mẹ́fà sì wọ́pọ̀ ní erúkùṣú galápagos ní ibi tí wọ́n ti mọ̀ wọ́n sí àwọn alángbá àpáta nígbà míràn wọ́n máa ń kówọn sí àye tropidurus wọ́n má ń rí àwọn tókù tí wọ́n ń pè ní pacific iguanas ní andes lọ́na òk...
microlophus atacamensis microlophus atacamensis náà atacamen pacific iguana jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángbá orí àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní chile
microlophus bivittatus alángba àpáta san cristóbal microlophus bivittatus jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù galápagos wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé tropidurus tẹ́lẹ̀
microlophus delanonis microlophus delanonis alángbà àpáta española tàbí alángbà àpáta hood wọ́pọ̀ ní erékùṣù galapagos ti española wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé tropidurus tẹ́lẹ̀
microlophus duncanensis microlophus duncanensis jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù galápagos ti wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé tropidurus tẹ́lẹ̀
tropidurus boilerplate seealso>ẹ tún wo microlophus tropidurus jẹ́ ìdílé àwọn ẹranko afàyàfà àwọn ẹ̀yà alángbá ẹbí tropiduridae orí ilẹ̀ náà wà ní ìdílétropidurus tropidurus jẹ́ ìdílé tị ọ jẹ́ ẹbí tropiduridae tí ó sì jẹ́ ẹbí alángbá iguanian àgbègbè ibi tí ó wà ati ibùgbé a máa ń rí àwọn ẹ̀yà ìdílé tropidurus ní òkè o...
isbn international standard book number isbn jẹ́ àìlẹ́gbẹ́ oùnka tí wọ́n fi ń dá ìwé mọ̀ ni ede yoruba o tumọ si nọmba iwe itọju iwe-mimọ international
international standard book number
van hollaway van hollaway jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ní ilẹ̀ amẹ́ríkà ìrìnàjò iṣẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá hollaway ní olórí àwọn akọ́nimọ̀ọ́gbá college football ní bethany terrible swedes ní agbègbè lindsborg kansas ó di ipò yí mú láti ọdún 1974 títí dé 1975 gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá ìwé ìrántí rẹ̀ fiwàn wípé bethany ...
microlophus grayii microlophus grayii tí wọ́n mọ̀ sí alángbá floreana jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù galápagos ti floreana wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé tropidurus tẹ́lẹ̀ ìpinlẹ̀ṣẹ̀ wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan grayii dá john edward gra...
microlophus habelii microlophus habelii tí wọ́n sábà mọ̀ sí alángbá àpáta marchena jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù galápagos ti marchena ìpinlẹ̀ṣẹ̀ wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan habelii dá simeon habel onímọ̀ àdáyébá ọmọ jamaní-amẹ́ríkà lọ́lá ìṣàsọ́tọ̀ wọ́n fí m habelii sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n w...
microlophus heterolepis microlophus heterolepis jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní chile àti peru
microlophus koepckeorum microlophus koepckeorum tí wọ́n mọ̀ sí frost's iguana jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní chile àti peru ìpinlẹ̀ṣẹ̀ wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan koepckeorum dá hans-wilhelm koepcke àtí maria koepcke tí wọ́n jẹ́ ọkọ àti ìyàwó onímọ̀ ẹyẹ ọmọ orílẹ̀ èdè jamaní tí wọ́n bí sị́ peru
microlophus occipitalis microlophus occipitalis ti knobbed pacific iguana jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní ecuador àti peru
microlophus pacificus microlophus pacificus èyí pacific iguana tí ó wọ́pọ̀ jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù galápagos ti pinta wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà tropidurus tẹ́lẹ̀
microlophus peruvianus microlophus peruvianus ti peru pacific iguana jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní ecuador peru àti chile wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé tropidurus tẹ́lẹ̀
microlophus quadrivittatus microlophus quadrivittatus ti pacific iguana onígun mẹ́rin jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí a máa ń rí ní peru àti chile
microlophus stolzmanni microlophus stolzmanni tí stolzmann's pacific iguana tàbí alángbá stolzmann jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní peru
microlophus tarapacensis tarapaca pacific iguana microlophus tarapacensis jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángbá ti ẹbí iguanidae ó wọ́pọ̀ ní chile
microlophus theresiae microlophus theresiae pacific iguana ti theresia jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní peru ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹranko tí a ní ní àgbáyé
microlophus theresioides microlophus theresioides orúkọ rẹ̀ gangan ní èdè spanish ni corredor de pica jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángbá tí ó wọ́pọ̀ ní chile
microlophus thoracicus microlophus thoracicus pacific iguana ti tschudi jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní peru
microlophus tigris microlophus tigris tàbí tiger pacific iguana jẹ́ àwọn irú alángba àpáta tí ó gbalẹ̀ ní peru
microlophus yanezi microlophus yanezi àwọn alángbá yanez jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní chilean matorral nínú orílẹ̀ èdè chile
àkójọ àwọn ẹranko afàyàfà àkójọ àwọn ẹranko afàyàfà àwon ẹranko elégungun tó wà ní ọ̀wọ́ àwọn ẹbí ẹranko afàyàfà tí ó dé àwọn ọ̀wọ́ ńlá mẹ́ta
aacocrinus aacocrinus tí wọ́n tún mọ̀ sí ìyẹ́ ìràwọ̀ jẹ́ òdòdó òkun tí a kò rí mọ́ lati ẹbí actinocrinitidae tàbí patelliocrinidae wọ́n ti fi hàn wípé ó tòrò mọ́ nkan elẹ́mí kan tí ó maa ń jẹ àwọn nkan ẹlẹ́mí tí ó bá kọjá láì rí wọn mg calcite wà lára rẹ̀ ó sì ń gbé ní òkè epifauna lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀yà mẹ́rìndínlógún ni ó...
aaglacrinus aaglacrinus jẹ́ ẹ̀yà crinoidea ní ìhà cladia tí a kò rí mọ́ wọ́n ti gbèrò wípé kò lè rín tòrò nkan elẹ́mí kan tí ó maa ń jẹ àwọn nkan ẹlẹ́mí tí ó bá kọjá tí magnesium calcite wà lára ibi tí ó le lára rẹ̀ àwọn ẹ̀yà lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀yà méjì ni ó wà nínú ìdílé yìí àwọn méjèèjì wà lábẹ́ orúkọ aaglaocrinus
abrotocrinus abrotocrinus jẹ́ jẹ́ ẹ̀yà crinoids tí a kò rí mọ́ àwọn àkọsílẹ̀ ohun ẹlẹ́mí díẹ̀ tókù wọ́n mọ ìdílé yìí nínú àwọn àkọsílẹ̀ ohun ẹlẹ́mí díẹ̀ tókù ti ìgbà eléèédú ti united states àti canada ọjó orí 3538 sí ọdún mílíọnù 3450 sẹ́yìn
argentina fish argentina jẹ́ ìdílé herring smelts àwọn ẹ̀yà lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀yà mẹ́tàdínlógún ni a mọ́ nínú ìdílé yìí
azubuike okechukwu azubuike godson okechukwu bí ní ọjọ́ kọnkàndínlógún oṣù kẹ́rin ọdún 1997 jẹ́ alágbàṣe agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ yeni malatyaspor ti turkey gẹ́gẹ́ bí a gbá ipò àárín ìrìnàjò iṣẹ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù a bíi ní ìlú katsina okechukwu gbá bọ́ọ̀lù fún bayelsa united àti ye...
herring smelt herring smelts tàbí àwọn argentine jẹ́ ẹbí argentinidae ti òkún smelts ìrísí wọn dàbí ti smelts ẹbí osmeridae ṣùgbọ́n ẹnu won kéré díẹ̀ wọ́n maa ń rí wọ́n nínú òkun káàkiri gbogbo agbayé wọ́n jẹ́ ẹja kékeré tí wọ́n maa ń dàgbà tó bí ní gígùn yàtọ̀ sí argentine títóbi argentina silus t́ ó maa ń tó bíi wọ́n...
acanthotheelia acanthotheelia jẹ́ ìdílé kòkúmbà òkún tí a kò rí mọ́ ṣùgbọ́n tí a ti rí tẹ́lẹ́ ni poland ní ìgbà triassic àwọn ẹ́yà tí ó wà nínú rẹ̀ ni acanthotheelia spinosa acanthotheelia spiniperjorata àti acanthotheelia anisica
achistrum achistrum jẹ́ ìdílé kòkúmbà òkún tí a kò rí mọ́ ṣùgbọ́n tí a ti rí tẹ́lẹ́ ni poland ní ìgbà triassic àti ní united states ìgbà eléèédú àwọn ẹ́yà tí ó wà nínú rẹ̀ ni achistrum nicholsoni àti achistrum ludwigi
agaricocrinus agaricocrinus jẹ́ ìdílé crinoid tí a kò rí mọ́ tí ó wà ní ẹbí coelocrinidae àwọn tí wọ́n ń gbé ní òkè epifaunal tí wọ́n ń tòrò mọ́ nkan tí wọ́n maa jẹ yìí wà ní ìgbà eléèédú àti àkókó osagean tí united states lati 3538 sí 3450 ma àpèjúwe bíi àwọn crinoid ẹ̀yà agaricocrinus maa ń ta mọ́ ojú ibi tóbà le
phasianidae phasianidae jẹ́ àwọn ẹyẹ tí ó ń gbé inú ilẹ̀ bi àwọn ẹyẹ àparò ẹye ìgà adìyẹ igbó àwọn adìyẹ ẹyẹ bí adìyẹ awó àti ẹyẹ pòpòndò ọ́pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹyẹ fún ìdáraya nió wà ní ẹbí yìí ẹbí yìí tóbi púpọ̀ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan wọ́n máa ń pín wọn sí àwọn mọlẹ́bí méjì phasianinae àti perdicinae nígbàmíràn wọ́n máa ń tọ́jú àwọn...
klaus biemann klaus biemann ọjọ́ kejí oṣù kọkànlá ọdún 1926 ọjọ́ kejí oṣù kẹfà ọdún 2016 jẹ́ ọ̀jọ̀gbón onímọ̀ chemistry ní massachusetts institute of technology ìṣé rẹ̀ dá lórí ìgbékalẹ̀ onínọmbà ní organic àti biochemistry wọ́n ti pèé ní bàbá organic mass spectrometry
david agard david a agard phd jẹ́ ọ̀jọ̀gbón ìmọ̀ biochemistry àti biophysics ní university of california san francisco ó gba oyè àkọ́kọ́ bs nínú ìmọ̀ molecular biochemistry àti biophysics lati yale university ó sí gba oyè phd rẹ̀ nínú ìmọ̀ biological chemistry lati california institute of technology iṣẹ́ rẹ̀ dá lórí ìm...
in-young ahn in-young ahn jẹ́ onímọ̀ ìjínlẹ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè south korea ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ korea tí ó maa kọ́kọ́ dé antarctica ó sì jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ asia tí ó maa ṣe olórí ibùdó antarctic king sejong station ó jẹ́ onímọ̀ ìbáṣepọ̀ oun ẹlẹ́mì ìsàlẹ̀ omi àti agègbè wọn ó sì ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀...
àwọn amino acid àwọn amino acid jẹ́ àwọn ohun tí ó ní carbon tí ó wúlò fún ara tí ó sì ní amine -nh2 àti carboxylic acid -cooh gẹ́gẹ́ bíi àwọn akójọpọ̀ fún iṣẹ́ ṣiṣe tí ó sábà maa ń ní ìsomọ́ lẹ́gbẹ́ pàtó fún amino acid kọ̀ọ̀kan àwọn ìdá ìpilẹ̀ amino acid tó ṣe kókọ́ ni carbon hydrogen oxygen àti nitrogen bípótilẹ̀jẹ́w...
nike peller nike peller jẹ́ òṣèré èdè yorùbá ọmọ orílẹ̀ èdè nàíjíríà àtí oní ìrújú orí ìtàgé ó jẹ́ ọmọ olóògbé professor peller nike jẹ́ olóyéyeye agbasaga ti ìlú erin osun tí ó jẹ́ ní ọdún 2010
jide kosoko ọmọba jídé kòsọ́kọ́ jẹ́ ògbónta òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè nàíjíríà ìgbà èwé àti ìrínàjò iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bíi ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínín ọdún 1954 ní ìlú èkó sí ìdílé ọlọ́ba kosoko ti erékùṣù èkó ó kàwé nípa okùn-òwò ní yaba college of technology ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe bí ọmọdé òṣèré ní ọdún...
glutamic acid glutamic acid àgékúrú sí glu tàbí e tí ó ń kóòdù fún gaa or gag jẹ́ α-amino tí wọ́n ń lò lati ṣèdá àwọn protein nínú ara ó ní α-amino lẹ́gbẹ́ kan èyí tí ó ní agbára −nh3+ lábẹ́ ààyé àti α-carboxylic acid lẹ́gbẹ́ kan èyí tí kò ní agbára −coo− lábẹ́ ààyé àti carboxylic acid tí ó somọ́ lẹ̀gbẹ́ tí a sì kó wọn...
n-acetylglutamic acid n-acetylglutamic acid agékúrú sí nacglu enzyme n-acetylglutamate synthase máa ń ṣẹ̀dá rẹ̀ nínú ara lati glutamic acid àti acetyl-coa arginine ni ó máa ń jẹ́ kí ìṣẹ̀dá yí bẹ̀rẹ̀ ìdàkejì rẹ̀ ní ìfi omi tú ẹgbẹ́ acetyl ka lọ́wọ́ enzyme tí ó ń jẹ́ hydrolase nacglu sọ carbamoyl phosphate synthetase di ...
aldh1a3 aldehyde dehydrogenase 1 family member a3 tí a tún mọ̀ sí aldh1a3 tàbí retinaldehyde dehydrogenase 3 raldh3 jẹ́ enzyme nínú àwọn ènìyàn tí aldh1a3 gene ń kóòdù fún iṣẹ́ rẹ̀ aldehyde dehydrogenase isozymes jẹ́ àwọn enzymes tí a rò wípé wọ́n ń ṣiṣẹ́ takuntakun ní pípa oró àwọn aldehyde tí ó jẹyọ nínú ètò ògógóró ...
aldh1l1 10-formyltetrahydrofolate dehydrogenase jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí aldh1l1 gene máa ń kóòdù fún ìwé àkàsíwájú <templatestyles src=refbegin/stylescss /> pmid pmid pmc pmid pmc pmid pmid pmid pmid pmc pmid
aldh1l2 aldehyde dehydrogenase 1 family member l2 ti aldh1l2 jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí aldh1l2 gene máa ń kóòdù fún aldh1l2 jẹ́ isoform nínú mitochondrial tí ó fẹ́ fara pẹ́ aldh1l1 tí ó máa ń sọ 10-formyltetrahydrofolate di tetrahydrofolate àti carbon dioxide
aldh3b2 aldehyde dehydrogenase family 3 member b2 jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí aldh3b2 gene máa ń kóòdù fún
aldehyde dehydrogenase 4 family member a1 delta-1-pyrroline-5-carboxylate dehydrogenase mitochondrial jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí aldh4a1 gene máa ń kóòdù fún
aldehyde dehydrogenase 5 family member a1 succinate-semialdehyde dehydrogenase mitochondrial jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí aldh5a1 gene máa ń kóòdù fún iṣẹ́ rẹ̀ protein yìí wà ní ẹbí aldehyde dehydrogenase ti àwọn protein gene yìí máa ń kóòdù fún succinic semialdehyde dehydrogenase tí ó gbójú lé nad+ ti mitochondr...
aldehyde dehydrogenase 9 family member a1 4-trimethylaminobutyraldehyde dehydrogenase jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí aldh9a1 gene máa ń kóòdù fún
aldh16a1 aldehyde dehydrogenase 16 family member a1 tí a tún mọ̀ sí aldh16a1 jẹ́ aldehyde dehydrogenase gene ìwúlò rẹ̀ fún ètò ìlera àwọn ìyípadà nínú spg21 acp33/maspardin gene ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú mast syndrome tí ó jẹ́ irú spastic paraplegia protein tí ó ń kóòddù fún spg21 gene ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú aldh16a1 enzyme
aldehyde dehydrogenase aldehyde dehydrogenases ec 1213 jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn enzymes tí ó ń ó ń mú ìtẹ̀síwájú bá fífi oxygen yíyọ hydrogen kún àwọn aldehyde
ìṣekúpa abraham lincoln john wilkes boot ṣekú pa ààrẹ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà abraham lincoln ní ọjọ́bọ̀ ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrìnlá ọdún 1865 nígbà tí ó lọ wo eré our american cousin ní ilé ìṣeré orí ìtàgé ford bí ogun abẹ́lé amẹ́ríkà ṣe ń lọ sí òpin ìpànìyàn yìí ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ karún tí balógun ti ológun dìmọlú ti gúúsù virgi...
assassination of abraham lincoln
anelloviridae anelloviridae jẹ́ ẹbí àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ mọ́ wọ́n kàwọ́n sí àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn tí ó légungun tí ó sì ní ẹ̀wù ìdáàbòbò tí o gbó dáradára tí ó rí róbótó tí igun rẹ̀ jọ ara wọn pẹ̀lú ogún igun tó jọrawọn àwọn ẹ̀yà wọ̀n yí jẹ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn t...
betatorquevirus betatorquevirus jẹ́ idile àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ mọ́ ni ebi anelloviridae ní ẹgbẹ́ ii in the baltimore classification ó ṣàkójọpọ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí tí a mọ̀ tẹ́lè sí tlmv ttv-like minivirus tàbí àwọn kòkòrò àìlèfojúrí midi ti torque teno pélébé àwọn ...
hesperentomidae the hesperentomidae are a family of hexapods in the order protura hesperentomidae jẹ́ ẹbí hexapods ní ẹgbẹ́ protura
protentomidae protentomidae jẹ́ ẹbí àwọn hexapod ní ẹgbẹ́ protura
acerentomidae acerentomidae jẹ́ ẹbí hexapods ní ẹgbẹ́ protura àwọn acerentomid ó ní ẹ̀yà fún èémí
antelientomon antelientomon jẹ́ ìdílé àwọn hexapod ní ẹgbẹ́ protura tí ó sì jẹ́ ìdílé kan ṣoṣo tí ó wà nínú ẹbí antelientomidae ó ní àwọn ẹ̀yà mẹ́ta
eosentomidae eosentomidae jẹ́ ẹbí àwọn hexapod ní ẹgbẹ́ protura àwọ́n eosentomid ní ẹ̀yà fún èémi wọn kò dàbí acerentomidae
sinentomon sinentomon jẹ́ ìdílé kan ṣoṣo tí ó wà ní ẹbí sinentomidae ní ẹgbẹ́ hexapod ẹgbẹ́ protura ó ní ẹ̀yà mẹ́ta àwọn ìtọ́kasí
fujientomon fujientomon jẹ́ ìdílé àwọn hexapo ní ẹgbẹ́ protura tí wọ́n kó sí ẹ̀bí tiè fujientomidae ó ní àwọn ẹ̀yà méjì àwọn ìtọ́kasí fujientomidae it contains two species
william harper oló́ṣèlú ilẹ̀ rhodesia
hesperentomon hesperentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí hesperentomidae
huhentomon huhentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí hesperentomidae
ionescuellum ionescuellum jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí hesperentomidae
condeellum condeellum jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí protentomidae
hinomotentomon hinomotentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí protentomidae wọ́n má a ń rí wọn ní gúúsù asia
neocondeellum neocondeellum jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí protentomidae
paracondeellum paracondeellum jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí protentomidae
protentomon protentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí protentomidae
proturentomon proturentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí protentomidae
acerella acerella jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
acerentomon acerentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
acerentuloides acerentuloides jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
acerentulus acerentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
alaskaentomon alaskaentomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
amazonentulus amazonentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
amphientulus amphientulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
andinentulus andinentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
australentulus australentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
baculentulus baculentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
berberentulus berberentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
bolivaridia bolivaridia jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
brasilentulus brasilentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
brasilidia brasilidia jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
callientomon callientomon jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
chosonentulus chosonentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
delamarentulus delamarentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
filientomon filientomon is jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
fjellbergella fjellbergella jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
gracilentulus gracilentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
huashanentulus huashanentulus jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae
imadateiella imadateiella jẹ́ ìdílé àwọn proturan nínú ẹ̀bí acerentomidae