raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
ayazi syndrome ayazi syndrome tàbí chromosome 21 xq21 deletion syndrome àmìn àrùn tí a maa ń rí bí ènìyàn bá ní àrùn choroideremia ìdití abínibí àti ìsanrajù ìmọ̀ nípa abínibírẹ̀ wọ́n ṣàpèjúwe bí ìbíni mọ́ ayazi syndrome jẹ́ x-linked recessive chm àti pou3f4 ni àwọn gíìnì tó sọnù ní ipò xq21 locus tí wọ́n wà àwọn ìtọ́k... |
bifid penis bifid penis tàbí okó méjì jẹ́ àrùn abínibí tí kò wọ́pọ̀ léyí tí genital tubercle méjì maa ń yọ jáde ìtàn sọọ́ di mímọ̀ wípé àwọn ọmọkùnrin tí wọ́n bí pẹ̀lú okó méjì maa ṣisẹ́ abẹ lati to okó wọ́n dáradára wọ́n tọ́ wọn bí obìrin tí wọ́n sì ṣiṣẹ́ abẹ fún wọn kí wọ́n lè dàbí obìnrin tí wọ́n a sí fi iṣẹ́ abẹ fí... |
diphallia diphallia penile duplication pd diphallic terata tabi diphallasparatus jẹ́ ohun àìbójúmu tí kò wọ́pọ̀ leyí tí ọmọ ìkókó maa ní okó méjì àkọsílẹ̀ àkọ́kọ́ tí a kọ́kọ́ rí ni tí johannes jacob wecker ní ọdún 1609 ìru nkan báyìí maa ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ní bíi 55 million àwọn ọkùnrin ní united states àwọn àrùn to ní ṣe... |
the guardian the guardian jẹ́ ìwé ìròyìn olójoojúmọ́ tí àtẹ̀jáde rẹ̀ ń wáyé ní ìlú èkó ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ilé iṣẹ́ guardian newspapers limited ni ó ń ṣakápò rẹ̀ |
trialeurodes trialeurodes greenhouse whitefly jẹ́ ìdílé àwon whiteflie tí ó tóbi nínú ẹbí aleyrodidae ẹ̀yà àádọ́ta lé mẹ́ta tí wọ́n gbà wọlé |
list of whitefly species aleyrodidae jẹ́ ẹbí hemipteran tí ó tóbi èyí tí àwọn whiteflie wà àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí tún wà níbẹ̀ *acanthaleyrodes callicarpae *acanthaleyrodes styraci *acanthobemisia distylii *acanthobemisia indicus *acaudaleyrodes africanus *acaudaleyrodes ebeni *acaudaleyrodes pauliani *acaudaleyrodes rachipo... |
ben murray-bruce ben murray-bruce jẹ́ oníṣòwò olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ìlà oòrùn balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ nàìjíríà ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú people's democratic party ó jẹ́ o... |
linux linux tí wọ́n ń pè báyìí jẹ́ ètò àwọn ọ̀nà iṣé ẹ̀rọ kọ̀mpútà tí ó dàbí unix tí ó bá posix mu tí wọ́n tòpọ̀ lábẹ́ lílo lọ́fẹ́ fún ìdàgbàsókè software àwọn ẹ̀yà linux tí a mọ̀ ni linux kernel ètò àwọn ọ̀nà iṣẹ́ kernel tí linux torvalds ṣàgbéjáde rẹ̀ ní ojọ́ karún oṣù ikẹwá ọdún 1991 free software foundation lo orúk... |
cellulitis cellulitis jẹ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí bacteria tí ó ní ṣe pẹ̀lú inú ipele awọ ara ó maa ń dojú kọ ipele tí ó wà láàrín inú àti ìta ara pẹ̀lú ìpele ibí olọ́rá nínú awọ ara àmì àti àpẹẹrẹ tí a fì lè mọ̀ pé àkóràn yìí ti wọ ara ní pípọ́n ròdòrodo ara tí ó sì maa ń fẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀ àwọn ààlà ibí pípọ́n yìí... |
bacterial vaginosis bacterial vaginosis bv jẹ́ àrùn òbò tí ó maa ń wáyé tí ìdàgbàsókè kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn tí à ń pè ní bacteria bá ti pọ̀jù ní ojú ara obìnrin àwọn ààmì àrùn yìí tí a maa ń sábà rí ní kí omi maa jáde ní ojú òbò tí ó sì maa ń rùn bí ẹja omi tí ó maa ń jáde yìí maa ń funfun tàbí kí ó ní àwọ̀ eérún o... |
paul émile chabas paul émile chabas ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1869 ọjọ́ kẹwá oṣù karún ọdún1937 jẹ́ olùyàwòrán ará faransé àti ọmọ ẹgbẹ́ académie des beaux-arts ìgbésíayé wọ́n bíi ní nantes ó sì kọ iṣẹ́ ọnà lábẹ́ william-adolphe àti tony robert-fleury ó kọ́kọ́ ṣe àfihàn iṣẹ́ rẹ̀ ní salon ní ọdún 1890 chabas gba ẹbùn prix... |
osborne theomun olsen osborne theomun olsen ọjọ́ kẹsán oṣù kẹfà ọdún 1883 ọjọ́ kẹsán oṣù kínín ọdún 1971 olùdásílẹ̀ art studios ní chicago illinois tí ó wà láti 1910 di 1973 ìgbésíayé rẹ̀ wọ́n bi osborne ní chicago illinois ní ọjọ́ kẹsán oṣù kẹfà ọdún 1883 àwọn òbí ẹ ni anna maria jensen 1854-1896 àti peder matthias ol... |
david a r white david a r white jẹ́ òṣèré filmu àti atọ́kùn filmu ará amẹ́ríkà |
ẹ̀sìn àgbọn ẹ̀sìn àgbọn tinh do cu si jẹ́ ẹ̀sìn tí wọ́n ti fòpin sí tí ó sì jẹ́ ẹ̀sìn kan tí wọ́n ń sìn ní ilú àgbọn ti gúúsù vietman níbi tí wọ́n ti dáa sílẹ̀ ní ọdún 1963 ẹ̀sìn yìí dá lórí ẹ̀sìn búdà àti ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ pẹ̀lú àwọn ẹ̀kọ́ nípa olùdásílẹ̀ nguyễn thành nam tí ó jẹ́ onímọ̀ ará vietman àwọn aláṣẹ vietman fi... |
coconut religion |
ísíakí folórunsọ́ adéwọlé |
gene wilder jerome silberman june 11 1933 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
òfin kòtò àkọ́kọ́ òfin kòtò àkọ́kọ́ tàbí òfin kòtò jẹ́ òwe tí ó sọ wípé tí o bá ba ara rẹ nínú kòtò kí o maa ṣe gbẹ́ ẹ síwájú síi ìtumọ̀ rẹ̀ ni wípé tí o ba bá ara rẹ ní ipò tí kò dára ki o dúró kí o sì ṣe àtúnṣe oun tí ò ń ṣe tẹ́lẹ̀ kí o má sẹ tẹ̀síwájú ibi tí ó ti jẹyọ oríṣiríṣi ibi ni wọ́n rò wípé òwe yìí ti jẹyọ ó ... |
law of holes |
jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b jẹ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn hepatitis b virus hbv tí ó maa ń dójú kọ ẹ̀dọ̀ ó lè fa àkóràn tí kò léwu àti èyí tí ó léwu ọpọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni kò mọ àwọn àmì tí a maa ń rí tí ó bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ àwọn míràn maa ń ṣe àìsàn lójijì tí ó sì maa ń mú èébì ara òfééfèé rírẹra ìtọ̀ dúdú àti inú... |
àwọn ọmọ áfríkà amẹ́ríkà |
hepatocellular carcinoma hepatocellular carcinoma hcc tí a tún pè ní malignant hepatoma jẹ́ àrùn jẹjẹrẹ inú ẹ̀dọ tó wọ́pọ̀ àwọn ìdí tí àrùn yìí lè fi wáyé ní nípasẹ̀ àkóràn kòkòrò jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b tàbí c àwọn ohun tó lòdì sára bíi ògógóró tàbí aflatoxin àwọn ìpò bíi hemochromatosis àti alpha 1-antitrypsin de... |
anna sui anna sui ìbílẹ̀ chinese 蕭志美 àgékúrú 萧志美 pinyin xiāo zhìměi japanese アナスイ bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 1964 jẹ́ aṣaralẹ́ṣọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà wọ́n pèé ní ìkan lára àwọn márún tí ó gbayì jùlọ ní bíi ọdún mẹ́wá sẹ́yìn tí ó jẹ́ pé ní ọdún 2009 ó gba ẹ̀bùn geoffrey beene lifetime achievement award láti cou... |
philippe de champaigne philippe de champaigne ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù karún ọdún 1602 ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1674 jẹ́ ayàwòrán ará faransé tí a bí sí brabançon tí ó jẹ́ olùgbéga ilé ẹ̀kọ́ faransé ó jẹ́ ara àwọn olùdásílẹ̀ académie de peinture et de sculpture ìgbésíayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bíi sí ẹbí òtòṣì kan ní brus... |
àfin beaumont àfin beaumont tí wọ́n henry i kọ́ sí gúúsù ọ̀nà àbáwọlé oxford ní ọdún 1130 gẹ́gẹ́ bí àfin ọba kí ó lè súnmọ́ ibi tí ọba ti ń rẹra ní woodstock nísìn ó jẹ́ ara àfin blenheim |
jon polito jonathan raymond jon polito 29 oṣù kejìlá 1950 1 oṣù kẹ̀sán 2016 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
oyún ṣíṣẹ́ |
andy serkis andrew clement andy serkis april 10 1964 je osere ara ilẹ̀ọba aṣọ̀kan |
ebute metta ebute metta jẹ́ agbèègbè ìlú èkó ní ìpínlẹ̀ èkó orílẹ̀ èdè nàìjíríà orúkọ ebute metta jẹ́ ọ̀rọ̀ yorùbá fún ibi tí ó jẹ́ etí òkun mẹ́ta ebute túmọ̀ sí etí òkun tí meta sì túmọ̀ sí mẹ́ta ìtàn wọ́n mọ ebute metta sí ṣíṣètò oúnjẹ àti àwọn aṣọ ó jẹ́ ibìkan ní ìlú èkó tí ó ti wà tipẹ́ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé tí ó wà n... |
baptist boys’ high school baptist boys’ high school jẹ́ ilé ìwé girama ní abeokuta ìpínlẹ̀ ògùn gúúsù-ìwọ oòrùn nàìjíríà ó ní àwọn akẹ́kọ ẹgbẹ̀rún lé ọgọ́rún ní ọdún 2011 sí 2012 àwọn akẹ́kọ yìí dínkù dé ìdajì láti 2155 ní ọdún 1998 sí 1999 látàrí láti ri wípé kí oun èlò fún ẹ̀kọ́ lè tó won bbhs wà ní ibùdó rẹ̀ ní oke-... |
jon lovitz jonathan michael jon lovitz july 21 1957 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
akarigbo of remo akarigbo ti remo tàbí olọ́run remo jẹ́ oyè ọba tí ọba yorùbá ti ilú sagamu maa ń jẹ ìlú yìí àti àwọn agbègbè rẹ̀ jẹ́ ara ilú tí wọ́n maá ń pè ní ìjẹ̀bú ìpinlẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ ọba ìlù remo ti wà tipẹ́ láti ìgbàtí tí ọmọ ọba ọ̀yọ́ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ obanta ti dá ilù ìjẹ̀bú sílẹ̀ àti ìgbà tí ọmọ ọba àkárìgbò ti w... |
hannah idowu dideolu awolowo hannah idowu dideolu awolowo àbísọ adelana ọjọ́ karùndínlọgbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1915 ojọ́ ọkàndínlógún oṣù kẹsán ọdún 2015 tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí hid jẹ́ ọmọ bíbí ìlú kékeré kan tí wọ́n ń pè ní ikenne ní ìpínlẹ̀ ògùn ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó kàwé ní methodist girls high school ní ìlú èkó ó ... |
amy poehler amy meredith poehler september 16 1971 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
protologism protologism ni a brand titun ọrọ |
high court of lagos state high court of lagos state jẹ́ ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní ìpínlẹ̀ èkó ó ní ẹ̀ka méjì ìkan wà ní erékùṣù èkó tí èkejì sì wà ní ikeja olóyè olóògbé conrad idowu taylor ní ó kọ́kọ́ jẹ́ adájọ́ àgbà ní high court of lagos state ní ọdún 1967 kí ó tó fẹ̀yìntì |
jackie chan jackie chan tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1954 jẹ́ òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọ̀kọrin ọmọ orílẹ̀ èdè china sinimá rẹ̀ máa ń dá lé ìjà afìpá àti gídígbò jà |
city hall lagos lagos city hall tí a mọ̀ sí gbọ̀gán ìlú èkó di dídásílẹ̀ ní ọdún 1900 ó kalẹ̀ sí agbègbè àwọn ará brazil ní àárín èkò níbi tí ọrọ̀ ajé ti ń lọ ó wà ní ẹ̀gbẹ́ king's college lagos st nicholas hospital lagos àti cathedral of the holy cross lagos gbọ̀ngán ìlú yìí jẹ́ olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ tí àwọn àgbègbè mí... |
king's college king's college lagos jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì ní ìpínlẹ̀ èkó wọ́n dáa síle\̣ ní ọjọ́ ogún oṣù kẹsán ọdún 1909 pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ́ mẹ́wá ní erékùṣù èkó lẹ́gbẹ́ tafawa balewa square ìlé ẹ̀kọ́ yìí maa ń gba ọkùnrin nìkan bíótilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn obìnrin díẹ̀díẹ̀ wà lára wọn a level àwọn akẹ́kọ hsc kí wọ́n tó ... |
badagry division badagry division jẹ́ ilé jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ fún ìṣètò ìpínlẹ̀ èkó nàìjíríà ìtàn nípa rẹ̀ badagry division jẹyọ nínú ìtàn ìbáṣepọ̀ láàrín orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti yúrópù tí ó sìjẹ́ ibi tí ọjà tí wọn ti ṣòwò ẹrú wà nígbà tí àwọn bìrìtìkó kó wọn lẹ́rú ó tún jẹ́ ibi tí àwọn ẹlẹ́sìn ìgbàgbọ́ ti kọ́kọ́ kéde ìyìn... |
steven seagal steven frederic seagal jẹ́ òṣèré àti atọ́kùn sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà |
khary payton khary payton may 16 1972 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
candido da rocha candido joao da rocha 1860 - 1959 jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ onílẹ̀ ayanilówó tí ó n water house tó wà ní àdùgbò von kakawa lagos island lagos tí ó tun ni ilé ìtura bonanza tí ó wà ní ìlú èkó da rocha jẹ́ ọmọ bíbí iléṣà tí wọ́n bí sí inú ebí joao esan da rocha tí ó jẹ́ ẹrú tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ... |
nguyễn chánh thi nguyễn chánh thi ọjọ́ kẹtàlélódún oṣù kejì ọdún 1923 ọjọ́ kẹtàlélódún oṣù kẹfà ọdún 2007 jẹ́ ológun ilẹ̀ vitenam arvn wọ́n mọ̀ọ́ sí àwọn ipa tí ó kó nínu fifipá gba ìjọba ní bí 1960 tí ó sì wà lára àwọn ológun tí o ṣe ìjọba gúúsù vietnam láti ọdún 1964 sí 1966 tí ó sì jẹ́ wípé nígbà tí ọ̀gá ológún òfúr... |
24607 sevnatu 24607 sevnatu jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
14189 sèvre 14189 sèvre jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
89264 sewanee 89264 sewanee jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
22815 sewell 22815 sewell jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
6586 seydler 6586 seydler jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
26971 sezimovo ústí 26971 sezimovo ústí jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
66671 sfasu 66671 sfasu jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
10458 sfranke 10458 sfranke jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
13921 sgarbini 13921 sgarbini jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
2263 shaanxi 2263 shaanxi jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
15427 shabas 15427 shabas jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
21745 shadfan 21745 shadfan jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
6566 shafter 6566 shafter jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
11944 shaftesbury 11944 shaftesbury jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
10014 shaim 10014 shaim jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
5619 shair 5619 shair jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
1648 shajna 1648 shajna jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
4618 shakhovskoj 4618 shakhovskoj jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
5959 shaklan 5959 shaklan jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
14322 shakura 14322 shakura jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
3408 shalamov 3408 shalamov jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
22640 shalilabaena 22640 shalilabaena jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
21814 shanawolff 21814 shanawolff jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
2510 shandong 2510 shandong jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
29467 shandongdaxue 29467 shandongdaxue jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
1994 shane 1994 shane jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
25058 shanegould 25058 shanegould jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
2197 shanghai 2197 shanghai jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
21402 shanhuang 21402 shanhuang jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
22817 shankar 22817 shankar jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
18838 shannon 18838 shannon jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
20812 shannonbabb 20812 shannonbabb jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
18670 shantanugaur 18670 shantanugaur jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
3139 shantou 3139 shantou jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
1881 shao 1881 shao jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
3832 shapiro 3832 shapiro jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
1123 shapleya 1123 shapleya jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
1902 shaposhnikov 1902 shaposhnikov jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
5543 sharaf 5543 sharaf jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
17092 sharanya 17092 sharanya jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
5580 sharidake 5580 sharidake jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
4074 sharkov 4074 sharkov jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
3694 sharon 3694 sharon jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
2416 sharonov 2416 sharonov jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
5426 sharp 5426 sharp jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
20481 sharples 20481 sharples jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
12593 shashlov 12593 shashlov jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
3027 shavarsh 3027 shavarsh jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
4510 shawna 4510 shawna jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
20296 shayestorm 20296 shayestorm jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
4625 shchedrin 4625 shchedrin jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
2377 shcheglov 2377 shcheglov jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
3886 shcherbakovia 3886 shcherbakovia jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
4870 shcherban' 4870 shcherban' jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
11450 shearer 11450 shearer jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
1196 sheba 1196 sheba jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.