raw_text
stringlengths
2
128k
joseph wayas joseph wayas tí wọ́n bí ní 21 may 1941 tó sì dágbére fáyé ní 30 november 2021 fìgbà kan jẹ́ olórí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tí orílẹ́-èdè nàìjíríà lásìkò tí nàìjíríà gba òmìnira lọ́wọ́ ìjọba ológun19791983 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí wayas ní basang obudu ìpínlẹ̀ cross river ní 21st may 1941 ó sì kẹ́kọ̀ọ́ ...
paul eyefian paul o eyefian je oniwaasu naijiria to n dunnu nigbagbogbo o je oluso-aguntan ogba adari ni idapo jccf fellowship alakoso nifes fellowship ati alaga ti igbimo idibo olominira omo ile-iwe paul eyefian wa labe adari archbishop dr v e arikoro jp ati pe o je oluso-aguntan ti a yan sipo ni ijo pentecostal afric...
mc casino lawre osarenkhoe tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ mc casino jẹ́ apanilérìn-ín ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di gbajúgbajà látàri pé ó jé aṣojú àṣà tó sì ń gbe lárugẹ apanilẹ́rìn-ín náà kúndùn láti máa fi àwọn fọ́nrán rẹ̀ pa àwọn ènìyàn lẹ́rìn-ín ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ university of benin uniben ni ó ti kékọ̀ọ́ gboy...
charles okocha charles okocha tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí igwe 2pac jẹ́ òṣèrékùnrin orílẹ́-èdè nàìjíríà tó gbajúmọ̀ fún ṣiṣe ẹ̀dá-ìtàn ọmọ burúkú nínú eré charles okocha jé ọ̀kan lára àwọn àwòkọ́ṣe fún 'idea challenge èyí tí nigeria billionaires network gbé kalẹ̀ ó gbégbá orókè nínú ìdíje ti vskit voice ní ọdún 2019 ìgbésí a...
kunle ajayi kunle ajayi june 16 1964 jẹ́ olórin ẹ̀mí ilẹ̀ nàìjíríà ó jẹ́ olòkọrin olùnfọn dùùrú olùwàásù lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwọ̀rán àti olùdarí akọrin ti ìjọ oníràpadàredeemed christian church of god
kingsley okonkwo kingsley okonkwo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1976 jẹ́ olùṣọ́-àgùntàn olùdámọ̀ràn àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀ àti olùṣọ́-àgùntàn ti ìjọ david's christian centre ó sì tún jẹ́ olùṣèdásílẹ̀ ìpérò tó jẹ́ mọ́ ọ̀rọ̀ ìfẹ́ ìbáṣepọ̀ àti ìgbéyàwó èyí tó máa ń wáyé ...
jerry eze jerry uchechukwu eze tí a bí ní ọjó̩ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdun 1982 jẹ́ olùṣọ-àgùntànìjọ kan ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà eze jẹ́ olùdásílẹ̀ streams of joy international àti olùdarí new season prophetic prayer and declaration nsppd at̀i ìpàdé orí afẹ́fẹ́
chukwuemeka cyril ohanaemere chukwuemeka cyril ohanaemere tí wọ́n bí 9 september 1982 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí odùméje jẹ́ àlùfáà ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria gẹ́gẹ́ bi i alábòójútó gbogboogbò ti the mountain of holy ghost intervention and deliverance ministryàti olórin ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ìgbésí ayé rẹ̀ odùméje ni a bí ní ìpí...
alhaji yahaya madawaki alhaji yahaya madawaki mfr obe dll oloye ti king george vi da lọ́lá ni oṣù kiini 1907 títí di ojo karùn-ún osu kẹfà 1998 jẹ́ gbajúmò òṣèlú orile-ede naijiria o ti fi igbakan je minisita fun ètò ilera madawaki ti ilorin ati atunluse ti erin-ile ni ìpínlẹ̀ kwara
augustine ukattah augustine ukattah tí wọ́n bí ní august 281918 tó sì ṣaláìsí ní january 271996 je oluko ile naijiria ati oloselu ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí augustine echewodor ukattah ní ahaba-oloko ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikwuano ní ìpínlẹ̀ ábíá ní august 28 1918 ukattah jẹ́ ọmọkùnrin kẹrin tí ukattah nkor abajuo ...
aminu tambuwal aminu waziri tambuwal tí a bí ní ọjó kẹ̀wá ọdún 1966 o jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ó ṣojú ẹkùn gúsù sókótó gẹ́gẹ bí asofin ni odun 2023 o sin gege bi gomina ipinle sokoto lati ọdun 2015 si 2023 o je ọmọ egbe oselu peoples democratic party leyin èyí o sin gege bi agbenuso kejila fun ile igbinmo asojusofin nàìj...
lazarus muoka lazarus muoka jé òlùsóagutan ní orilede naijiria ajihinrere pelu òǹkọ̀wé o je oludasile ati oludari fun the lord’s chosen charismatic revival movement ìgbésí ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ tó yàn láàyò wọ́n bí lazarus muoka sínú ìdílé catholic ní umuhu-okabia tó wà ní orsu lga ti orlu zone ní ìpínlẹ̀ ímò níbi tí ó ti l...
timothy oluwole obadare timothy oluwole obadare tí wọ́n bí ní oṣù kẹrin 1930 tí ó sì papòdà ní oṣù kẹta 2013je ajinhinrere am ohun mú àwòrán ni ìlù nàìjíríà àti ajinhinrere gbogbogbo ìjọ kristi àpọ́sítélì cac ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ ọbadare ni a bi ni ileṣa báyìí apakan ti ipinle osun guusu iwọ-oorun nàìjíríà david ati feli...
chris kwakpovwe chris kwakpovwe tí a bí ní ọjọ́ meédoògún oṣù kọkànlá ọdún 1961 jẹ́ ìránṣẹ́ onígbàgbò akọ́ṣẹmọṣẹ́ onìwósán elégbòogi ati onkọwe oun ni oludasile ati oluso-aguntan agba ti manna prayer mountain mpm ministry worldwide ti o wa ni ilu eko o tun jẹ onkọwe ti manna ojoojumọ wa olufọkansin ojoojumọ chris kwakp...
augustine ukattah
godman akinlabi godman akinlabi tí wọ́n bí ní 28 december 1974 jẹ́ olùṣọ́-àgùntàn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì tún jé òǹkọ̀wé asọ̀rọ̀-ní-gbangba àti onímọ̀-ẹ̀rọ òun ni olùdarí ìjọ the elevation church ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí godman akinlabi ní december 28 1974 ìlú igbo-ora ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ló ti wá ìyẹn ...
matthew aṣímọlówó
tunde bakare tunde bakare tí wọ́n bí ní november 11 1954 jẹ́ wòlíì àti olùṣọ́-àgùntàn ti orílẹ́-èdè nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nípa ìmọ̀-òfin ní university of lagos ó sì fi ṣiṣé látàri ṣíṣí ilé-iṣẹ́ tirẹ̀ sílẹ̀ ó padà fi iṣẹ́ náà sílẹ̀ láti lọ ṣe iṣẹ́ olúwa óṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i amòfin àgbà ní deeper life bible church àmọ́...
done p dabale done peter dabale tí wọ́n bí ní april 26 1949 tó sì ṣaláìsí ní august 26 2006 jẹ́ olùdásílẹ̀ ìjọ united methodist church ní orílẹ́-èdè nàìjíríà umcn lásìkò tó jẹ́ bíṣọ́ọ̀bù iye àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ ìjọ náà lọ láti 10000 sí 400000 ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tó lọ ni
jeremiah omoto fufeyin jeremiah omoto fufeyin tí wọ́n bí ní 15 february 1971 sí burutu ní ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ olùdásílẹ̀ àti wòlíì àgbà ti ìjọ christ mercyland deliverance ministry cmdm effurun ìpínlẹ̀ dẹ́ltà nàìjíríà ó ṣe ìdásílẹ̀ ìjọ náà ní 3 april 2010 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ẹbí rẹ̀ wọ́n bí jeremiah...
emmanuel iren nigerian gospel artist and pastoremmanuel aniefiok iren wọ́n bí ní ojo kejidinlogun osu opeodun 1989 tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí emmanuel iren jẹ́ oníwàásù àti olórin ẹ̀mí ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀celebration church international cci èyí tí olú-ìjọ wọn wà ní ìpínlẹ̀ èkó ní nàìjíríà ní ọdún 2018 ó...
benjamin kalu benjamin okezie kalu jẹ́ gbajúgbajà olóṣèlú omo orílẹ̀-èdè nàíjírìa tó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi igbákejì olórí ilé ìgbimọ̀ aṣòfin àgbà orílẹ̀ èdè naìjíríà láti ọdún 2023 ìdìbò rẹ sí ipò yìí ní awon akegbe re nile igbimo asofin abga fowosi kalu n ṣe aṣojú fun agbègbè àpapò bende tí ó si mu ero ati ohun ti awon e...
khalil halilu khalil halilu tí a bí ní ọjọ́ 29 oṣù kẹwàá ọdún 1990 jẹ́ ọmọ ilé-iṣẹ́ ìṣòwò àti alámọ̀já ìmọ̀-ẹ̀rọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òntàjà àti igbákejì aláṣẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ àti olùdarí àgbà ti national agency for science and engineering infrastructure naseni ààrẹ bola tinubu yàn án sí ipò yìí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹsà...
mc edo pikin gbadamosi agbonjor jonathan tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí mc edo pikin jẹ́ apanilẹ́rìnín ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ihievbe ìlú tí ó wà ní ìpínlẹ̀ edo ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2021 mc edo pikin gba àmì-ẹ̀yẹ ti the humor award tha fún ìsọ̀rí ti apanilẹ́rìnín ní ọdún náà iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ap...
taiwo odukoya daniel taiwo odukoya 15 june 1956 7 august 2023 jẹ́ àlùfáà tí pentecostal ni nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òlùdásílẹ̀ àti àlùfáà àgbà tí the fountain of life church tí ó si wà ní ilupeju lagos àti pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ tótó egbarin ènìyàn ní ọdún 2010s taiwo odukoya wọn bí ní ọjọ́ kàrúndínlógún oṣù kẹfà ọd...
madam koi koi madam koi koi tí a tún mọ̀ sí lady koi koi miss koi koi madam high heel tàbí madam moke ní ghana àti miss konkoko ni tanzania jẹ́ òkú nínú àwọn ìtàn ìgbàanì ti ilẹ̀ nàìjíríà àti áfíríkà tó máa ń ṣẹ̀rùbà wọ́n ní ilé-ìgbé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti ilé-ìgbọ̀nsẹ̀ ní àwọn ilé-ìwé lálẹ́ africa
de general joshua sunday tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ de general jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà kan ó díbọ́ bí aṣiwèrè kó ba lè fún àwọn ènìyàn tó bá ràn án lọ́wọ́ lówó iṣẹ́ tó yàn láàyò apanilẹ́rìn-ín náà ń rí owó látara ṣíṣàgbéjáde fọ́nrán lórí facebook àti youtube ó mú jackie chan gẹ́gẹ́ bí àwòkọ́...
climate action africa climate action africa tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí cma jẹ́ àwùjọ tí ó ń jà fún climate resilience ilé iṣẹ́ àwùjọ yìí kalẹ̀ sí ní gra ikeja ìpínlẹ̀ èkó oluchi grace àti chukwuemeka fred agbata ni ó da kalẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kèje ọdún 2021
hauwa ali hauwa ali o ku ni ọdun 1995 jẹ onkọwe ọmọ orilẹede naijiria ti a mọ si awọn iwe aramada rẹ ti n ṣawari awọn igbesi aye awọn obinrin musulumi ati igbega awọn ibeere nipa awọn idiyele islam ati ominira awọn obinrin iwe aramada ti o mọ julọ julọ destiny gba ẹbun delta fun itan arosọ igbesi aye a bi i ni gusau ni...
blood sisters fíìmù 2022 blood sisters je ere naijiria ti gbe jade ni odun 2022 ere yii je akoko ere naijiria ti yo wo series awon agba osere ibe ni ini dima-okojie ati peelu ramsey nouah kate henshaw wale ojo kehinde bankole deyemi okanlawon gabriel afolayan tope tedela peelu awon elere miiran awon apa meerin ere na j...
arabinrin ẹjẹ jara 2022
jude dibia òǹkọ̀wé orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríàjude dibia tí wọ́n bí ní 5 january 1975 ní ìpínlẹ̀ èkó ní nàìjíríà jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2007 ó gba ẹ̀bù ti ken saro-wiwa fún ìwé ìtàn-àròsọ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ unbridled ètò-ẹ̀kọ́ dibia kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní yunifásítì ìlú ìbàdàn ó sì gboyè ba nínú ẹ̀kọ́ mod...
natasha bowen natasha bowen jẹ́ olùkọ́ àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà-tó tan-mọ́-àwọn-ará-wales ó ń kọ àwọn ìwé aláìdálérí-ìtàn-gidi fún àwọn ọ̀dọ́ wọ́n mọ̀ ọ́n fún ìwé ìtàn-àròsọ rẹ̀ skin of the sea tó jẹ́ ìwé ìtàn-àròsọ tó ń tà jù ní new york ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí natasha bowen sí cambridge...
jhumpa lahiri nilanjana sudeshna jhumpa lahiri tí wọ́n bí ní july 11 1967 jẹ́ òǹkọ̀wé ti indian àti american tí ó gbajúmọ̀ fún àwọn ìtàn kékeré rẹ̀ ìwé ìtàn-àròsọ àti àròkọ rẹ̀ ní èdè gẹ̀ẹ́sì àti ní èdè italy à̀tòjọ ìtàn kékeré rẹ̀ ni interpreter of maladies 1999 tó gba ẹ̀bùn pulitzer prize for fiction àti ẹ̀bùn pen/he...
oṣù kínní
àtojọ awọn èso
abimbola adelakun abimbola adunni adelakun born 15 september </link> jẹ́ akọ̀wé ọmọ nàìjíríà igbesiaye ọmọ bíbí ní ìbàdàn gúúsù ìwọ̀ oòrùn nàìjíríà ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ní fásitì ti ìbàdàn níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ yege pẹ̀lú ìwé ẹ̀rí àti master of arts ní ìbánisọ̀rọ̀ àti iṣẹ́ èdè o gboye gboye gege bi phd dimu ni ijó ati itage n...
jimoh oyewumi ajagungbade iii ọba jimoh oladunni oyewumi ajagungbade iii yoruba jímọ̀ ọládùnní oyèwùmí 27 may 1926 12 december 2021 fìgbà kan jẹ́ sọ̀ún àti olórí ìlú ògbómọ̀ṣọ́ fún ọdún méjìdínláàádọ́ta 48 years títí di ìgbà tó kú ní ọdún 2021 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ibi tó ti ṣẹ̀ wá oba jimoh oladunni oyewumi ajagungbade ii...
emeka enejere emmanuel nnaemeka enejere 19442016 was a nigerian academic and a political scientist he was the 14th pro-chancellor and chairman of the governing council of the yunifásítì ilẹ̀ nàìjíríà nsukka and a former president of the national union of biafran students in the midst of the nigerian civil war early lif...
pius n okeke pius nwankwo okeke ti a bi ni 30 oṣu kẹwa ọdun 1941 jẹ awòràwọ ati olukọni ni orilẹ-ede naijiria ti o ṣe alabapin lọpọlọpọ si iwadii aaye afirika igbesi aye ibẹrẹ pius nwankwo okeke ni a bi ni 30 oṣu kẹwa ọdun 1941 ni oraukwu okeke lo si ile iwe alakobere ni oraukwu nibi ti o ti gboye ni math leyin naa lo ...
mahmoud abdel-aty mahmoud abdel-aty jẹ olukọ ọjọgbọn ara egipti ti mathimatiki ati imọ-jinlẹ alaye ni ile-ẹkọ giga sohag ati ẹka iṣiro ni ilu zewail ti imọ imọ-ẹrọ ati innovation o jẹ ẹlẹgbẹ ti a yan ati igbakeji alakoso ariwa afirika tẹlẹ ti ile-ẹkọ giga ti imọ-jinlẹ ti afirika alakoso igbimọ orilẹ-ede egypt fun inter...
àwọn ará ìbàràpá ethnic groupàwọn ará ibarapa jẹ́ ẹ̀ya yorùbá tí ó wà ní apá gúúsù ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ orúkọ àwọn ará ìlú yìí jẹ yọ láti ará èso bàrà tí a mọ̀ sí egusi ibara èyí tí ó jẹyọ nínú ìtàn tí àwọn alábàágbé wọn pa bí i àwọn egba ibadan àti àwọn oyo pé wọ́n ń dáko ní agbègbè náa
femi orenuga kenny oluwafemi gbolahan ademola femi orenuga tí wọ́n bí ní 18 march 1993 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè gẹ́ẹ̀sì tí ó ń gbá a ní ààrin-gbùngbùn iṣẹ́ tó yàn láàyò southend united orenuga tí wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ lewisham ní london darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù southend united ní ọdún 2006 lẹ́yìn tí ó wú ẹgbẹ́ náà ...
òǹkò àwọn ará òǹkò tí a tún mọ̀ sí ará òkè ògùn jẹ́ ẹ̀yà yorùbá jé àwọn tó ń gbé apá kan òkè ògùn ní erékùṣù ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́
lawuyi ogunniran láwuyì ògúnníran 5 november 1935 21 september 2020 jẹ́ òǹkọ̀wé eré ní nàìjíríà tó ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ní èdè yorùbá eré rẹ̀ eégún aláré jẹ́ iṣẹ́ tí gbogbo ayé tẹ́wọ́ gbà ó sì jẹ́ ìwé tí a nílò fún kíláàsì lítíréṣọ̀ yorùbá ní ọ̀pọ̀ ilé ẹ̀kọ́ girama ní nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé ẹ̀kọ́ ti jẹ́ ìyàsọ́tọ̀ l...
richard bamisile richard olufemi bamisile ẹni tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí bafem wọ́n bí i ní 27 september 1965 jẹ́ olóṣèlú nàìjíríà tí ó sì jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tó ń ṣojú agbègbè gúúsù èkìtì ii ó tún jẹ́ agbẹnusọ ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ èkìtì nígbà kan rí ìjókòó kẹta ó wà lára àwọn olùdíje fún ipò gómìnà nínú ètò ìdìbò ab...
abideen olasupo olasupo abideen opeyemi tí àbí ní october 17 1993 ní ìlú ifọ́n ní ìpínlẹ̀ osun ó jẹ́ oníṣòwò orílè èdè nàìjíríà ó jẹ́ olùdásílè ilé-iṣẹ́ opab gas àti brain buiders youth development initiative bbydi ó sì jẹ́ ìkan lára alágbàwí sdgs un pe olasupo abideen láti sọ̀rọ̀ ní 2023 economic economic and social c...
sam aluko samuel àlùkò august 18 1929 february 7 2012 jẹ́ gbajúgbajà ọmọ nàìjíríà onímọ̀ ètò ọrọ̀ ajé àti ọ̀mọ̀wé tó kọ oríṣìíríṣìí àwọn ìwé tí ó yànnàná àwọn àlàkalẹ̀ ìjọba lórí àwùjọ àti ètò ọrọ̀ ajé àlùkò tún kó ipa olùdámọ̀ràn fún àwọn aṣíwájú olóṣèlú bí i obafemi awolowo àti sani abacha ànfàní ìkẹyìn yìí ni wọ́n l...
david abioye david olatunji abioye je omo naijiria ti a bi ni march 111961o je onigbagbo onkowe ati oniwaasu oun niigbakeji adari ijo fun ijo olorun igbagbo aye kaakiri agbaye iyen living faith church o je bisoobu ati oniwaasu agba ni ijo to wa ni abuja eyi ti a n pe ni ilu goseni ti o ni iwon omo ijo oke meji ati abo ...
olusoji fasuba olusoji adetokunbo fasuba ti a bi ni 9 july 1984 je elere ori paapa ologorunibuso o gbe gba oroke laarin awon elere ile adulawo ni iseju aaya 985 titi ti akanni simbine fi gba ipo naa ni july 2021 pelu iseju aaya 984 iberepepe aye re wọ́n bí fasuba sí sapele ní ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ní orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríà òun ...
tunde adebimpe babatunde omoroga adebimpe listen ⓘ ti wón bí ní february 25 1975 ó je olórin orílè-èdè améríkà olórin-orinrin òsèré adarí àti olorin wiwo ti a mo si gege bi olori olorin ti brooklyn -based band tv lori redio
oyin adejobi oloye oyin adejobi 19262000 jẹ́ òǹṣèré ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà orúkọ rẹ̀ oyin tunmọ si honey ni èdè gẹ̀ẹ́sì ó kọ oríṣiríṣi itan o si kópa nínú eré orí ìtàgé yorùbá lori ẹrọ amóhùnmáwòrán ati ninu fíìmù ọ ṣe ìgbéyàwó pẹlu òṣèré grace oyin-adejobi ti wọn sì jọ wà pọ̀ títí di ọjọ́ ikú rẹ̀ pàápàá jùlọ o gbajumo...
abimbola abolarinwa abímbọ́lá ayọ̀dèjì abọ́lárìnwá tí wọ́n bí ní 1979 jẹ́ oníṣègùn ọmọ nàìjíríà ó jẹ́ urọ́lọ́jístì obìnrin àkọ́kọ́ ní nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ a bí abímbọ́lá ní ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ìlú ọba uk fún ìyà rẹ̀ tí ó jẹ́ agbẹjọ́rò bàbá rẹ̀ sí jẹ́ ọmọ ógun òfuurufú àti dókítà onísẹ́ abẹ abọ́lárìnwá jẹ́ ọmọ bíbí ì...
lanre buraimoh lanre buraimoh kẹ́kọ̀ọ́ iṣẹ́-onà ìlẹ̀kẹ̀-híhun lọ́wọ́ àwọn òbí rẹ̀ olóyè jimoh buraimoh àti àlàkẹ́ buraimoh tí wọ́n jẹ́ gbajúgbajà onílẹ̀kẹ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti òkè òkun ẹ̀ṣọ̀ òun àrà tí àwọn ẹ̀yà yorùbá ilẹ̀ adúnláwọ̀ ń fi ìlàkẹ̀ ìbílẹ̀ dá sí adé bàtà àti ọ̀pá ìtìlẹ̀ àwọn ọba aládé ni ó ṣokùnfà ì...
chin ce chin ce tí wọ́n bí ní ọdún 1966 jẹ́ ònkọ̀wé ewì ìtàn-àkọ́ọ́lè àti àròsọ àti olóòtú àwòrán ìgbésíayé rẹ̀ o ti kọ ẹ̀kọ́ ní ilé-ìwé ti ìlú calabar ó jẹ́ ònkọ̀wé ti ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ ìtàn-mẹ́ta tí àkọ́leh rẹ̀ ń jẹ́ children of koloko gamji college àti the visitor àwọn iṣẹ́ rẹ̀ chin ce tún jé ònkọ̀ọ̀wé ti àwọn ipele mẹ...
pius nwankwo okeke pius nwankwo okeke ti a bí ní ọjọ́ ọgbọ́n oṣù kẹwá ọdún 1941 jẹ amọrawo àti olùkọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ṣe alábàápín lọpọlọpọ sí ìwádìí ààyè afíríkà à mọ ọ si bàbá tí astronomy ní nàìjíríà ìgbésí aye ibẹrẹ pius nwankwo okeke ni a bí ni ọjọ́ ọgbọ́n oṣù kẹwá ọdún 1941 ni oraukwu okeke lo si ile ...
philip begho philip begho tí a bí ní ọjọ́ 11 oṣù kiní ọdún 1956 jẹ́ oǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè naìjíríà òṣèré oǹkọ̀wé fún àwọn ọmọ oǹkọ̀wé ìtàn kúkurú àti akéwì ó ti kọ ju ìwé ogójì lọ a bí i ní warri ipinle delta itsekiri ni baba rẹ̀ ìyá a rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ẹlẹ́yàmẹyà ó gba ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga rẹ̀ ní king's college èkó ó sì g...
babatunde lawal salako nigerian academic babatunde lawal salako born 23 july 1959 jẹ akọkọ ọgá àgbà dókítà oníṣègùn òyìnbó ni ile-eko gíga university ìbàdàn chief medical director of the university college hospital ibadan ni ọdún 1978 sí ọdún 1984 òjé akọkọ olùdarí college of medicine university ti ibadan láàrin ọdún 2...
bidemi olaoba abidemi ayodeji ogunmolu tí a tún mọ̀ sí bidemi olaoba jẹ́ olórin ìhìnrere àti akọrin wọ́n mọ̀ ọ́n gẹ́gẹ́ bí òǹkọrin ìhìnrere ní ìlànà fújì ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ wọ́n bí olaoba ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹwàá ọdún 1991 sínú ìdílé kírítẹ́nì mẹ́fà ni wọ́n jẹ nínú ìdílé náà ní ìlú èkó orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó wá...
moses bliss akọrin moses bliss uyoh enang tí gbogbo ènìyàn mọ sí moses bliss tí a bí ní oṣù kejì ọjọ́ ogún ọdún 1995 jẹ́ akọrin ìhìnrere nàìjíríà adarí orin àti ònkọ̀wé orin ó tún jẹ́ òlùdásílẹ̀ spotlite nation aami akọọlẹ nàìjíríà moses bliss kọ́kọ́ ṣe ifilọlẹ akọkọ rẹ ní oṣù kìíní ọdún 2017 tí àkọlé jẹ́ “e no dey fal...
nikki laoye oyenike laoye tí a mọ iṣẹ rẹ sí agbohùn olórin sílẹ̀ olórin níẹnití o máa ṣe ohun kan fún àwọn ènìyàn o máa n ko orin sí lè oníjó òṣèré ní tí a mọ̀ ipa takuntakun tí òun kò nínú orin atí eré orí ìtàgé gẹ́gẹ́ bí agbohùn olórin sílè ilé iṣé orin laoye o tí gbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ bí obìnrin tó dáńgájiá nínú o...
moses bliss moses bliss uyoh enangti ọpọlọpọ awọn ẹniyan mọ si moses bliss wọn bi ni ogunjo osu kejiodun 1995o je akọrin ọmọ oriledẹ niajiriaada esin ati oluko orino je oludasile spotlite nation ile ise orin orilede naijiria
sinach osinachi kalu okoro egbu tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí sinach àbí ní ọjọ́ ọgbọ́n oṣù kẹta ọdún 1972 ó jẹ́ olórin ìlú nàìjíríà akọrin àti olórí olùsìn àgbà tí ó tí ń ṣiṣẹ́ fún bí ọgbọ́n ọdún ó jẹ́ akọrin àkókò tó kọ́kọ́ de ipò billboard christian songwriter chart fún ọ̀sẹ̀ méjìlá ẹ̀mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní wọ́n yan orin rẹ̀ ó sì...
onos ariyo onoriode ebiere ariyo tí a mọ̀ sí onos ariyo jẹ́ akọrin àti akọrin tí ó da lórílẹ̀ ẹ̀dẹ̀ nàìjíríà a mọ̀ ọ́n jùlọ sí orin ìyìn rẹ̀ “alagbara” tí ó jẹ́ àkórí orin tí ọ kọ tí ọ̀gbẹ́ni wilson joel bá a jẹ́ agbéjáde rẹ̀ ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni oṣù kẹsàn án ọdún 2018 o jẹ́ ẹni kan tí a dárúkọ lára àwọn tí o jẹ́ ...
ayo vincent ayodele enitan vincent tí a bí ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kínní ọdún 1980 tí a mọ̀ ní iṣẹ́-ìṣère bi ayo vincent jẹ́ olórin ìhìnrere nàìjíríà kan akọrin-akọrin àti òǹkọ̀wé ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin ní 2012 lọ́dún 2012 pẹ̀lú ìtúsílẹ̀ àwo orin àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ìdánilẹ́kọ̀ọ́ èmi ni tìrẹ ìgbésí ayé ibẹrẹ àti ẹ̀kọ́ ayodele ní ...
minisita guc gift ugochukwu christopher tí a bí ní october 8 1993 ó jẹ́ akọrin ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà olórin àti àwọn tí ó máa ń kọ orin àwọn onigbagbọ ti a mọ sì minister guc ó jẹ́ olùdámọ̀ nígbà tí ó ṣe álúbọ́ọ̀mù rẹ̀ ni oṣù kejìlá ọdún 2020 with the hit tracks all that matters desperate and yours he officially began...
loyola college ibadan
abdin mohamed ali salih abdin mohamed ali salih faas ftwas fiwra larubawa عابدين محمد علي صالح ti a bi ni 1944 ọjọgbọn imọ-iṣe ilu ilu sudan kan ni yunifasiti ti khartoum ati amoye unesco kan ni awọn orisun omi igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọl a bi salih ni wad madani sudan ni 1944salih darapo mo university of khartoum ni 196...
segun awolowo nigerian lawyer born 1963olúṣẹ́gun awólọ́wọ̀ jr wọ́n bí i ní 27 september 1963 jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ nàìjíríà ó jẹ́ alákòóso àgbà fún nigerian export promotion council láti ọdún 2013 dé ọdún 2021 ó jẹ́ ọmọ-ọmọ àgbà olóṣèlù nàìjíríà nnì olóyè obafemi awolowo ní oṣù keje ọdún 2021 wọ́n panupọ̀ dìbò yàn-án gẹ́gẹ...
tina fey elizabeth stamatina tina fey tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1970 jẹ́ òṣerébìnrin aláwàdà ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà fey wà lára àwọn tí ó ko eré nbc sketch comedy tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ saturday night live láti ọdún 1997 títí di 2006 òun ni ó sagbátẹ̀rù sitcom 30 rock 20062013 2020 àti erénetflix tí àkọ...
ahmed gomaa ahmed radwan ahmed gomaa ahmed radwan jẹ olùkọ́ ọjọgbọn ara egipti ti imọ-ẹrọ imọ-ẹrọ àti àwọn imọ-iṣe imọ-iṣe ní olùkó ti imọ-ẹrọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga cairo egypt o jẹ ẹlẹgbẹ ti a yan ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí imọ-jinlẹ afirika ọmọ ẹgbẹ agba ti institute of electrical and electronics engineers o jẹ olùdarí ile-iṣẹ ìṣ...
mose bìlísì 0 moses bliss uyoh enang tí gbogbo ènìyàn mọ sí moses bliss tí a bí ní oṣù kejì ọjọ́ ogún ọdún 1995 jẹ́ akọrin ìhìnrere nàìjíríà adarí orin àti ònkọ̀wé orin ó tún jẹ́ òlùdásílẹ̀ spotlite nation aami akọọlẹ nàìjíríà moses bliss kọ́kọ́ ṣe ifilọlẹ akọkọ rẹ ní oṣù kìíní ọdún 2017 tí àkọlé jẹ́ “e no dey fall my ...
láwuyì ògúnníran
richard bamisile
olusoji fasuba
abímbọ́lá abọ́lárìnwá
lanre buraimoh
damilola sunday olawuyi damilola sunday olawuyi san fciarb jẹ́ agbani-nímọ̀ràn káàkiri àgbáyé ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ òfin òǹkọ̀wé àti agbaniníyànjú lórí ọ̀rọ̀ epo-rọ̀bì iná ìwa-ohun-àlùmọ́nì àti òfin òun ni igbá kejì adarí yunifasiti afe babalola ado ekiti nigeria wọ́n fún ọ̀jọ̀gbọ́n ọjọgbọn ọlawuyi ní ìgbéga sí ipò ọ̀jọ...
rajaona andriamananjara rajaona andriamananjara faas ftwas 1 oṣù kejìlá ọdún 194330 oṣù kẹsán 2016 jẹ olùkọ́ malagasy ti àwọn imọ-jinlẹ àwùjọ àti ti ọrọ ajé o jẹ oludasile àti olùdarí gbogbogbo ti malagasy institute of planning techniques àti alága ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti orílẹ̀ èdè madagascar ti arts àwọn lẹta àti àwọn s...
bayo ojo christopher adebayo ojo san fìgbà kan jẹ́ attorney general ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì tún fìgbà kan jẹ́ olórí nigerian federal ministry of justice ó jẹ́ amòfin ó sì láṣẹ láti ṣiṣẹ́ ní nigeria england àti wales ó tún jẹ́ senior advocate of nigeria ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ ojo wá láti ife-ijumu kogi stat...
neymar neymar da silva santos júnior ti a bi 5 kínní 1992 ti a mọ si neymar júnior tabi mononymous bi neymar jẹ agbabọọlu alamọdaju ara ilu brazil kan ti o ṣere bii iwaju fun ẹgbẹ agbabọọlu pro league saudi pro al hilal ati ẹgbẹ orilẹ-ede brazil olukọni ibi-afẹde ati elere-iṣere olokiki fun aṣa iṣere rẹ ti o wuyi o jẹ ...
kamal shaddad kamal shaddad larubawa كمال شداد ti wọn bi ni ọdún 1935 jẹ olùkọ́ ọjọgbọn ara ilu sudan pelu imọ-jinlẹ oniroyin àti olùdarí ere ìdárayá o jẹ alága ẹgbẹ bọọlu afẹsẹgba sudan ju ogun ọdún lọ laarin ọdún 1988 ati 2021 ibẹrẹ ìgbésí aye àti ẹkọ kamal hamid shaddad ní wọn bí ni el-obeid north kurdufan sudan ní ...
muhammad mustapha olaroungbe akanbi muhammad mustapha olaroungbe akanbi san tí wọ́n bí ní 24 january 1971 tó sì ṣaláìsí ní 20 november 2022 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ẹ̀kọ́ òfin ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti igbá kejì olùarí kwara state university ó fìgbà kan jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ senior advocate of nigeria àti nigeria bar association ì...
fadwa taha fadwa abd al-rahman ali taha tí orúkọ rẹ̀ ní èdè lárúbáwá jẹ́ فدوى عبد الرحمن علي طه ti a bi 23 ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹwàá ọdún 1955 agbègbè arbaji ní ìpínlẹ̀ gezira ní orílẹ̀-èdè sudan ó jẹ́ olùkọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìtàn sakaani ní ilé-ẹ̀kọ́ university of khartoum igbesiaye igbesi aye ibẹrẹ ati ...
abdellatif berbich abdellatif berbich faas larubawa عبد اللطيف بربيش may 17 19421 january 2015 jẹ olùkọ́ ọjọgbọn ti oogun inu o jẹ alága idasile ti nephrology ile-iṣẹ moroccan akowe yẹ ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìjọba ilu morocco àti aṣojú ilu morocco si algiers ẹkọ berbich ní a bí ní fez morocco ní 17 may 1934 o lọ si àwọn ...
mubarak shaddad mubarak al-fadil shaddad larubawa مبارك الفاضل شداد 19151980 je alamọdaju iṣoogun ti ara ilu sudan ati oloselu ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nínú iṣẹ́ ìkọ́bí àti gynecology nígbẹ̀yìngbẹ́yín ó di olùdarí ilé ìwòsàn ìkọ́ni omdurman o kopa takuntakun ninu ẹgbẹ iṣoogun ti sudan ati pe o ṣe ipa ninu iyika o...
medlar mespilus germanica ti a mọ si medlar tabi medlar ti o wọpọ jẹ igbo nla kan tabi igi kekere ninu idile rosaceae awọn eso igi yii ti a tun pe ni medlar ni a ti gbin lati awọn akoko romu nigbagbogbo wa ni igba otutu ati jẹun nigbati o ba jẹ o le jẹ ni aise ati ni ọpọlọpọ awọn ounjẹ ti a ti jinna nigbati iwin mespil...
farida fassi farida fassi faas larubawa فريدة الفاسي jẹ ọjọgbọn moroccan tí ẹkọ fisiksi ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga mohammed v ní rabat o jẹ oludasilẹ ti ìlànà afirika fún fisiksi ìpìlẹ̀ ìpìlẹ̀ àti ọmọ ẹgbẹ ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti imọ-jinlẹ afirika igbesi aye ati ẹkọ fassi ni à bi ní larache nibiti ó ti lọ si ilé-ìwé arin àti gíga ...
ladoke akintola university of technology
nosa olórin nosa omoregie tí a mọ̀ sí nosa jẹ olórin naijiria akọrin àti òṣẹ̀ré o ti wa ni lọwọlọwọ wole si warner music group african alabaṣepọ chocolate city igbesi aye ibẹrẹ nosa omoregie tí a mọ̀ sí nosa a bi ní ọjọ́ mẹ́rin ẹ́rìndìnlọ́gbọ̀n oṣù kejì 1981 ó jẹ́ ọmọ ìlú benin ìpínlẹ̀ edo ó kọ́ ẹ́kọ́ imò-ẹ̀ro ni yuni...
muhammad al-mahdi al-majdhub muhammad al-mahdi al-majdhub 1919 - 3 march 1982ti a tún le pe ní al-maghut tabi al-majzoub jẹ́ olókìkí akéwì ara ilu sudan ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eniyan mọ bi ọkan ninu awọn aṣáájú-ni sudanese ewì àti kí ó ti wa ní ka fún jíjẹ ọkan ninu àwọn akọkọ ewi ti sudanese arabic oríkì àti sudanism àwọn í ...
aster gebrekirstos aster afwork gebrekirstos faas twas twas jẹ onimọ-jinlẹ ethiopia ati ọjọgbọn ti agroforestry ni ile-iṣẹ agrofogestry cortaforestry icraf igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ atunmọ gelekerkos ni a bi ni shire tigray etiopia bi ọmọ akọkọ ti idile ti meje o ni ero ti di dokita ṣugbọn awọn abajade ile-iwe giga rẹ k...
annona nutans annona nutans jẹ́ ẹ̀yà ti ọgbin nínú ìdílé annonaceae ó jẹ́ abínibí sí argentina bolivia brazil àti paraguay robert elias fries onímọ̀-jinlẹ̀ ará ìlú sweden tí o kọ́kọ́ ṣàpèjúwe ẹ̀dá náà ni ìpílẹ̀ṣẹẹ̀ sọ orúkọ rẹ̀ lẹ́hìn àwọn peduncles recurved èyítí ó fún àwọn òdodo ní nodding </link> ni latin irisi àpèj...
apricot apricot je eso tabi igi ti o nso eso órí eya orisirisi lati inu genus prunus nigbagbogbo apricot wa lati eya p armeniacasugbon eso ọrịsi eya ninu prunus sect armeniaca le je apricots etymology apricot koko farahan ni ede geesi ni 16th orudun gegebi abrecock lati middle french aubercot tabi nigbamii abricot lati...
annona paludosa annona paludosa jẹ́ ẹ̀yà ti ògbin nínú ìdílé annonaceae ó jẹ́ abínibí si brazil french guiana guyana suriname àti venezuela jean baptiste christophore fusée aublet onímọ̀-oògùn faransé àti onímọ̀-jinlẹ̀ tí o kọ́kọ́ ṣàpèjúwe ẹ̀dá náà ni ìpílẹṣẹ̀ sọ orúkọ rẹ̀ lẹyìn swampy </link> ni latin ibùgbé àpèjúwe ó...
sara ibrahim abdelgalil sara ibrahim abdelgalil arabic </link> jẹ dokita kan ti o da lori uk ati alagbawi ijọba tiwantiwa ti o ni ipa ninu awọn ipilẹṣẹ ajeji ti sudan ọmọ ẹgbẹ kan ti awọn onisegun ti sudan fun awọn ẹtọ eda eniyan o tẹnumọ aabo ọmọde o si ṣe alabapin ni itara lakoko awọn ehonu ara ilu sudan 20182019 ati...
banana melon ogede elegede jẹ iru heirloom elegede ni genus cucumis ti o wa lati bi igba 1880 ni ilẹ united states àpèjúwe o wọn ati iwọn ni ipari orúkọ rẹ wà láti elongated rẹ apẹrẹ tọkasi ati awọ ofeefeeti o se iranti ogede kàn bakanna bi orun ogede ti o lagbara eran rirọ re je awọ salmoni ati pe a sọ pé o ni adun ti...
garcinia cowa garcinia cowa ti a mọ si eso kowa tabi mangosteen cowa jẹ ohun ọgbin ti o ti wa nigba lailai o jẹ eso aláwọ̀ ewe asia india bangladesh myanmar malaysia vietnam laos cambodia ati guusu iwo oorun china igi náà ti wa ni ikore lati inu igbẹ fún àwọn eso ati awọn ewe yi o jeunti a lọ ní agbègbè àwọn òdodo fẹ o...
gaya melon gaya melon ti a tun mo si ivory gaya snowball sweet snowball ghost dinosaur dinosaur egg snow leopard matice matisse sugar baby ati silver star melons je kékeré sí irúgbìn oyin ti iwọn alabode ni idagbasoke ni akọkọ ni japan ati korea ati ni bayi dagba ni china mexico gúsù california ati south america àpèjúw...
ọkọ ofurufu pan am 914 ofurufu pan am 914 jẹ irokuro ti o sọ pe douglas dc-4 kan parẹ lẹhin igbati o ti lọ ni ọdun 1955 ati pe o tun balẹ lẹẹkansi ni ọdun mẹta lẹhinna itan naa ti jẹ olokiki lori intanẹẹti ti o ṣe ifihan lori awọn ikanni bii imọlẹ imọlẹ ìtàn ọrọ aṣiwadi naa sọ pe pan am douglas dc-4 pẹlu awọn arinrin-a...