raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
pierre abelard |
janez drnovsek janez drnovsek may 17 1950 february 23 2008 a bí ní ọdún 1950 ó jẹ́ olóòtú ìjọba slovenia ní 1992 sí 2002 lẹ́yìn èyí ni ó di àrẹ ilẹ̀ náà ní ọdún 1999 ni àìsàn kan ń bá a jà ní kíndìnrín ẹ̀kọ́ nípa ‘economics’ ni ó kà ó sì di ọmọ ilẹ́ asòfin ilẹ̀ slovenia ni ọdún 1986 iṣẹ́ ribiribi ni ó ṣe láàrin ọdún mẹ... |
mohammed yunus muhammad yunus bẹ̀ngálì pipe ojoibi 28 june 1940 je omo ilè bangladesh wón bí i ní 1940 fún ebí olówó kan ní chittagong gosimíìtì ni bàbá rè ìyá rè jé sofia khatun mama rè yìí máa n ran àwon òtòsì lówó ìwà yìí sì ran mohammed nígbà tí òun náà dàgbà ó dí ilé-ìfowópamó tí a ti lè máa yá àwon òtòsì lówó síl... |
ede yoruba |
napoleon bonaparte <ns>0</ns> <revision> <parentid>544362</parentid> <timestamp>2021-04-27t121130z</timestamp> <contributor> <username>agbalagba</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> napoléon bonaparte 15 august 1769 5 may 1821 jẹ́ olórí ológun àti adarí òṣèlú àti ọmọ bíbí ìlú c... |
àwọn ogun napoleon ogun napoleon ìjàgbara tí a ń pe ní revolution tí ó ṣẹlẹ̀ ní france jẹ́ kí fance ní ọ̀tá púpọ̀ ní ìlú òyìnbó èyí ni ó sì fa ogun tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin 1792 sí 1815 tí ó fẹ́rẹ̀ máa dáwó dúró ní àsìkò ogun yìí ilẹ̀ faransé ní ọ̀gágun kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ napoleon bonaparte ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni napoleon ṣẹ́... |
konrad adenauer wọ́n bí konrad adenauer ní 1876 ó kú ní 1967 òun ni chancellor west german federal republic ní 1949 sí 1963 òun ni ó dá christain democratic party sílẹ̀ òun sì ni alága rẹ̀ láti 1945 títí di 1966 lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun jẹ́mánì tán ó fún jẹ́mánì ní òfin constitution tí ó fi ni lọ́kàn balẹ́ ó sì jẹ... |
kàlẹ́ndà gregory kalenda gregory ni kalenda ti o n je lilo julo kakiri |
oṣù osù jemó ìgbà tàbí àkókò tí a n lo ìwé-ìwo ojó fún tí àyípadà rè sì máa n pé bíi ojú ojó tí ó sì farapé bí òsùpá se n sisé osù àti òsùpá ní ìbásepò tó dánmórán kí a tólè mo bí osù se n sisé a gbódò ní òye púpò nípa bí òsùpá se n sisé òdiwòn tí òsùpá àti osù fi n sisé kòju ókàn dín lógbòn sí métà lé láàdóta ojó lo 2... |
people's democratic party <ns>0</ns> <revision> <parentid>571115</parentid> <timestamp>2023-06-12t180358z</timestamp> <contributor> <username>enitanade</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> peoples democratic party pdp ẹgbẹ́ dẹmokrátíkì àwọn aráàlú jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orí... |
pdp <ns>0</ns> <revision> <parentid>532124</parentid> <timestamp>2020-04-25t214334z</timestamp> <contributor> <username>emausbot</username> </contributor> <minor /> <comment>bot fixing double redirect to people's democratic party</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
alfred adler alfred adler jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè austria wọ́n bí adler ní ọdún 1870 ó kú ní ọdún 1973 is ó jẹ́ oníṣègùn àrùn ọpọlọ tàbí wèrè psychiatrist òun ni ó dá ilé-ẹ̀kọ́ tí ó n jé ‘school of individual psychology’ sílẹ̀ ọ̀gbẹ́ni freud ni ó kókó n tè lé sùgbón ó yapa kúrò ní òdò rè lọ́dún 1911 ó tako ì... |
robert adam robert adam wọ́n bí adam ní 1728 ó kú ní 1792 yaléyalé architect ni ọmọ ilẹ̀ scotland ni ọkùnrin mẹ́rin ni àwọn òbí rẹ̀ bí ó jẹ́ ọkan nínú wọn díẹ̀ lára àwọn ilé tí ó yà ni harewood house york osterley park kedleston hall derbyslire luton hoo bedfordshire àti kenwood |
john adams john adams je oloselu omo ile amerika wọ́n bí adams ní 1735 ó kú ní 1826 òun ni ó jẹ president ilẹ̀ àméríkà lẹ́yìn washington òun ni ó kọ́kọ́ lọ ṣe ambassador ilẹ̀ oní-republic tuntun yìí ní ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì |
john couch adams john couch adams wọ́n bí adams ní 1819 ó kú ní 1892 ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ni onímọ̀ ìṣirò mathematics ni astronomer sì ni pẹ̀lú òun àti leverrier astronomer ọmọ ilẹ̀ faransé kan ni wọ́n jọ gba ogo ṣíṣe àwárí neptune ní 1846 òtọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n ṣe iṣẹ́ tí wọ́n gba ògo rẹ̀ yìí |
samuel adams wọ́n bí adams ní ọdún 1722 ó kú ní 1803 olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ àmẹ́ríkà ni tí ó ń fẹ́ kí àyípadà wa boston ni wọ́n ti bí i láti nǹkan bíi 1765 ni ó ti ń sọ pé ẹni tí kò bá ní aṣojú kò gbọdọ̀ san owó-orí no taxation without representation ó gbé ‘boston tea-party’ ga ní 1776 ó fi ọwọ́ sí ìwé òmìnira declaration of... |
william adams william adams wọ́n bí adams ní 1564 ó kú ní 1620 iṣẹ́ ọkọ̀ ojú omi navigation ni ó ń ṣe dillingham kent ni wọ́n ti bí i ní ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì òun ni ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ tí yóò lọ sí japan shogun ieyasu ní ìfẹ́ sí i gidi ni nítorí ìdí èyí wọn fi ibi tí àwọn gẹ̀ẹ́sì àti dutch ti lè máa ṣòwò lélẹ̀ ní japan el... |
jane addams jane laura addams a bí addams ní 1860 ó kú ní 1935 ọmọ ilẹ̀ àméríkà ni onímọ̀ nípa ẹ̀kọ́ tí wọ́n ń pè ní sociology ni òun ni ó dá hull house chicago sílẹ̀ ní 1889 |
joseph addison joseph addison je olukowe omo ile geesi wón bí addison ní 1672 ó kú ní 1719 ònkòwé ni addison olósèlú sì ni pèlú ó kópa nínú ‘taller’ òun àti steele ni wón sì jo dá ‘spectator’ sílè |
adelard ará bath adelard ara bath tabi adelard de bada latin adelardus bathensis c 1080 c 1152 je omowe ara ilegeesi ni orundun 12th scholar o gbajumo fun ise akoko re ati fun iyipadaede awon iwe sayensi pataki ni iworawo itorawo imoye ati mathimatiki latede griki ati larubawa si ede latin lati atejade larubawa latibe ... |
olú agúnlóyè olu agunloye ‘geophysicist’ ni dr olú agúnlóyè ‘ administrator’ sì ni wón bí dr agúnlóyè ní ojó kerìndínlógún osù késàn-án odún 1948 wón bí i ní erusu-àkókó ní ìpínlè ondó ó kàwé ní university of ibadan láàrin 1971 sí 1974 unversity of reading uk ní 1974 àti massachusetts institute of technology òun ni cor... |
ìyípo |
naijiria |
egbe oselu olominira ti puerto rico |
ibadan |
abuja |
obafemi awolowo |
alumíníọ̀mù chemical element with atomic number 13 alumíníọ̀mù tabi aluminomu e wo spelling labe je apilese kemika kan ninu adipo boron to je funfun bi fadaka to se mo o ni ami-idamo al ati nomba atomu 13 ko le yo ninu omi fun ra ara re aluminiomu je onide to po repetejulo ninu igbele aye ati iketa to po repetejulo nib... |
irin irin je àdàlú ni pataki julo idẹ pelu akoonu adú larin 02 and 17 or 204 ni iwuwosi adu ni o dinwoju lati se adalu mo idẹ sugbon a tun le lo adalu awon apilese miran manganisi kromiomu banadiomu ati wolframu adu ati awon apilese miran n sise bi imule sinsin lati dena ifo ninu atomu ayonu |
tld |
la <ns>0</ns> <revision> <parentid>387859</parentid> <timestamp>2013-03-08t133434z</timestamp> <contributor> <username>addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> migrating 68 interwiki links now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> la je amioro orile-ede internet ti t... |
lb lb je ti orile-ede lebanon |
ke |
kg kg je ti ile kyrgyzstan |
kh kh ni amioro orile-ede ti top-level domain lori internetcctld fun cambodia |
ki ki |
km |
kn kn je ti ile saint kitts ati nevis |
kp |
kr kr je ti orile-ede guusu korea |
kw kw |
nf nf ile erékùsù nọ́rúfọ́lkì |
ne ne |
nc nc |
na na |
mz mz je ti ile mozambique |
my my je ti malaysia |
mx mx je ti meksiko |
mw mw je ti orile-ede malawi |
mv mv je amioro orile-ede ti internet fun top-level domain cctld fun orile-ede maldives |
mu |
lc lc ni amioro orile-ede lori internet ti top-level domain cctld fun saint lucia |
li li jẹ́ ti ilẹ̀ líktẹ́ństáìnì |
lk lk je ti ile sri lanka |
lr lr je ti ile liberia |
ls |
lt lt |
mt mt |
ms ms |
mr mr |
mq |
mp mp is the internet country code top-level domain cctld for northern mariana islands |
mo |
lu lu je amioro orile-ede top-level domain cctld fun internet ti luxembourg |
lv lv ni amioro orile-ede top-level domain cctld lori internet fun latvia |
ly ly je ti orile-ede libya |
ma |
mc mc ni amioro orile-ede top-level domain cctld ori internet fun monaco |
md md je ti ile moldofa |
me me je amioro internet fun ile montenegro |
mg |
mh mh ni amioro orile-ede ti internet fun top-level domain cctld fun marshall islands |
mk mk |
ml ml ni amioro orile-ede lori intrnet fun mali |
mm mm ni àmì ọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè ti ìpele tí ó ga jùlọ lórí ẹ̀rọ ayélujára cctld fún burma lónìí gẹ́gẹ́bí ìṣọ̀kan ilẹ̀ myanmar ó jẹ́ fífifún ní ọdún 1997 síwájú 1989 àmì ọ̀rọ̀ iso 3166-1 fún burma ní bu ṣùgbọ́n bu cctld kọ̀ jẹ́ lílò rí rárá |
mn mn je ti ile mongolia |
julius nyerere julius kambarage nyerere 13 april 1922 - 14 october 1999 fi igba kan je aare ile tanzania ati ti tangayika tele |
bòtswánà <ns>0</ns> <revision> <parentid>575751</parentid> <timestamp>2023-10-04t020023z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> bòtswánà lóníbiṣẹ́ bíi o... |
ìhà ìwọ̀-oòrùn |
1 e10 m² to help compare orders of magnitude of different geographical regions we list here areas between 10000 km² and 100000 km² see also areas of other orders of magnitude definition 1 e+10 m² = formula_1 m² |
perú peru je orile-ede ni apa guusu amerika lima ni oluilu |
àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè bí àwọn ènìyàn wọn se pọ̀sí list figures indicated by un estimate are based on the july 1 2009 estimate by the united nations department of economic and social affairs population division |
port harcourt port harcourt tabi ebute harcourt ugwe ocha ni èdè igbo oborokiri ni ede ijo je ilu ni naijiria ati oluilu ipinle rivers |
kàdúná kàdúná je ilu ni naijiria ati oluilu ìpínlẹ̀ kàdúná |
gb gb gb je alfabeti yoruba pataki a b c d e ẹ f g gb h i j k l m n o ọ p q r s ṣ t u v w x y z |
gúúsù amẹ́ríkà gúúsù amẹ́ríkà |
guusu amerika |
rakunmi |
hàítì haiti je orile-ede ni apa ariwa amerika ni erekusu karibeani ti a mo si hispaniola |
gámbíà gambia tabi orile-ede olominira ile gambia je orile-ede ni apa iwoorun afrika |
liberia làìbéríà tabi orile-ede olominira ile làìbéríà je orile-ede ni iwoorun afrika o fi ègbé kan ilè sàró tí a mò si sierra leone ní ìwǫ oòrùn orílę èdè guinea ni gúúsù ati orílę èdè côte d'ivoire ní ìlà oòrùn etí òkun làìbéríà kún fún ijù igi mangrove nìbitì ilę nínú loun pęlú èrò kékeré ję kìkì ijù tí ó na apá sí ... |
senegal sẹ̀nẹ̀gàl tabi orile-ede olominira ile senegal je orile-ede ni iwoorun afrika senegal ni okun atlantiki ni iwoorun mauritania ni ariwa mali ni ilaorun ati guinea ati guinea-bissau ni guusu sinu die lo ku ko yipo gambia ka patapata si ariwa ilaorun ati guusu ibi to se ku nikan ni eti okun atlanti gambia ifesi il... |
ilaoorun afrika |
iwoorun afrika |
àríwá áfríkà |
kristina fermandez de kirchner |
kristina fernandez de kirchner |
godwin babátúnde kofi akran godwin babatunde kofi akran a bí ọba akran ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1936 lọ sí salvation army school kakawa lagos láàrin 1946 sí 1947 methodist school badagry àti methodist teachers training college ìfàkì-èkìtì láàrin 1956 sí 1957 ó lọ sí international press institute university of... |
tunji braithwaite tunji braithwaite je oloselu omo ile naijiria lọ́ọ́yà ni dr t́únjí braithwaite olóṣèlú sì ni wọ́n bí dr braithwaite ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1943 òun ni ó dá nigeria advanced party nap tí wọ́n ti parẹ́ sílẹ̀ ó gbé àpótí fún ipò ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ grassroots democratic advan... |
káyọ̀dé ẹ̀ṣọ́ bobakayode eso 18 september 1925 - 16 november 2012a bí justice kayọde èsó ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1925 ó lọ sí holy trinity school iléṣà láàrin 1933-1939 àti trinity college durban láàrin 1949-1953 wọ́n pè é sí bar ní lincoln inn london ní 1954 òun ni chief judge àkọ́kọ́ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní we... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.