raw_text
stringlengths
2
128k
a-q gilbert bani tí wọ́n bí ní august 1 1986 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì jẹ́ a-q jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè naijiria àti akọrinsílẹ̀
greg grunberg gregory phillip grunberg tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù keje ọdún 1966 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi eric weiss nínú eré abc tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ alias matt parkman nínú eré nbc tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ heroes temmin snap wexley nínú ' àti ' àti phil nínú a star is born ó farahàn ...
leslie schofield leslie schofield tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejìlá ọdún 1938 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britain tí ó gbajúmọ̀ ní united kingdom fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi jeff healy nínú soap opera eastenders ó kó ipa yìí láàrin ọdún 1997 sí 2000 ó farahàn nínú eastenders gẹ́gẹ́ bi brain wicks ní ọdún 1988 àti 1989 schofield...
garrick hagon garrick hagon tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1939 jẹ́ òṣèré ọmọ orilẹ̀-èdè britain àti canada ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi biggs darklighter nínú star wars a new hope àpẹẹrẹ àwọn eré tí ó ti kópa ni batman spy game me and orson welles àti the message òun ni ó kópa ky nínú eré the mu...
pernilla august pernilla august orúkọ tí àwọn òbí rẹ̀ fun ni mia pernilla hertzman-ericson tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì ọdun 1958 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ̀-èdè sweden ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní sweden ó sì ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú ingmar bergman ó gba àmì-ẹ̀yẹ best actress ní ayẹyẹ c...
deep roy gurdeep roy orúko ibí rẹ̀ ni mohinder purba tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù kejìlá ọdún 1957 tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí deep roy jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè kenya àti britain nítorí pé ko ga tàràgíga rẹ̀ ko ju lọ ó ma ń sábà kópa àwọn ènìyàn tí kò ga nínú àwọn eré bí àpẹẹrẹ gẹ́gẹ́ bi teeny weeny nínú the neverending story àt...
blaqbonez emeka akumefule tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ blaqbonez jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà
chinko ekun oladipo olamide emmanuel tí wọ́n bí ní 13 september 1993 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì jẹ́ chinko ekun jẹ́ olórin àti akọrin sílẹ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè látiobafemi awolowo university
da emperor fasasi mobolaji gaius tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ da emperor jẹ́ olórin òṣèrékùnrin àti akọrinsílẹ̀ tó wá láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà
dj ab haruna abdullahi tí wọ́n bí ní 30 december 1993 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dj ab jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà
illbliss tobechukwu ejiofor tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ illbliss jẹ́ olórin àti oníṣòwò ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun sì tún ni adarí àgbà fún ilé-iṣẹ́ 'the goretti company'
ian jazzi ian frederick oshodi tí wọ́n bí ní 30 march 1986 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ ian jazzi jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè ghana tótan mọ nàìjíríà jẹ́ olórin òṣèrẹ́kùnrin àti oníṣòwò
ladipoe ladipo eso tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ladipoe tàbí poe jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríàní 28 february 2017 ladipoe tẹwọ́bọ̀wé láti darapọ mọ́ ẹgbé-olórin mavin records
lyrikal jesse james enoch tí wọ́n bí ní 14 september 1983 tí orúkọ ìnagijẹ̀ rẹ̀ jẹ́ lyrikal jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà agbórinjáde àti akọrinsílẹ̀
mode 9 babatunde olusegun adewaletí wọ́n bí ní june 14 1975 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ modenine jẹ́ olórin ní ọdún 2014 ó ṣàgbéjáde orin kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ super human pẹ̀lú akọrin ti orílẹ̀-èdè jamaica kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ canibus
canibus canibus jẹ́ orúkọ ìnagijẹ́ fún germaine williams tí wọ́n bí ní december 9 1974 jẹ́ olórin
àtọjọ àwọn olórin tàkásúfèé ilẹ̀ nàìjíríà
odumodublvck tochukwu gbubemi ojogwu tí wọ́n bí ní 18 october 1993 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ jẹ́ odumodublvck jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà
pepenazi opeyemi gbenga kayode tíwọ́n bí ní 16 april 1988 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì jẹ́ pepenazi jẹ́ olórin tàkásúfẹ̀é ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà
phyno chibuzo nelson azubuike tí wọ́n bí ní 9 october 1986 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ jẹ́ phyno jẹ́ olórin olórin tàkásúfèé àti agbórinjáde ti orílè-èdè nàìjíríà phyno ti kọrin pẹ̀lú àwọn olórin bí i olamide wizkid davido timaya flavour ruggedman bracket j martins àti mr raw
flavour chinedu okoli tí wọ́n bí ní 23 november 1983 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ flavour n'abania tàbí flavour jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà
ibrahim tahir nigerian politician ibrahim tahir tí ó kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kejìlá ọdún 2009 jẹ́ onímọ̀ àyíká sociologist oǹkọ̀wé àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè ní ètò-òṣèlú ẹlẹ́ẹ̀kejì nigeria bákan náà ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ẹgbẹ́ alákatakítí kaduna mafia kí ó tó dárapọ̀ mọ́ òṣèlú ó jẹ́ onímọ̀ àyíká tí ó gbajúmọ̀ nínú òye ...
ruggedman michael ugochukwu stephens tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ruggedman jẹ́ olórin tàkásùféè ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó wá láti ohafia ipinle abia
bracket bracket jẹ́ olórin orílè-èdè nàìjíríà méjì kan tí wọ́n ń kọ orin afropop àti rb oŕkọ àwọn olórin méjèèjì yìí jẹ́ obumneme ali smash àti nwachukwu oziokovast
vector olanrewaju ogunmefun tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ vector jẹ́ olórin tàkásúfèé orílẹ̀-èdè nàìjíríà
ycee oludemilade martin alejo tí wọ́n bí ní 29 january 1993 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ ycee jẹ́ olórin tàkásúfèé ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà
kaduna mafia loose group of businessmen and military officers in kaduna nigeria kaduna mafia kì í ṣe ẹgbẹ́ ọ̀daràn bí kò ṣe ẹgbẹ́ àwọn olókowò òṣìṣẹ́ ìjọba àwọn onímọ̀ àti àwọn ológun láti ihà àríwá nigeria tí wọ́n ń gbé ní kaduna tàbí tí wọ́n ń ṣòwò ní kaduna tí ó jẹ́ olú-ìlú àgbègbè apá àríwá nígbà náà ní ìparí sáà è...
ado gwanja ado isah gwanja tí wọ́n bí ní 22 january 1990 jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti òṣèrékùnrin nínú àwọn fíìmù àgbéléwò ti apa gúúsù ilẹ̀ nàìjíríà
ajimovoix drums oguntade adewale damola tí wọ́n bí ní 27 june 1989 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ajimovoix drums jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà agbórinjáde àti elére irinṣẹ́ orin lóríṣiríṣi
ali jita ali isah jita tí wọ́n bí ní 15 july 1983 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ali jita jẹ́ olórin hausa ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà
ayra starr oyinkansola sarah aderibigbe tí wọ́n bí ní 14 june 2002 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ ayra starr jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n bí ní orílẹ̀-èdè benin ó jẹ́ olórin tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ nípa ṣíṣe àkọtúnkọ àwọn orin olórin lórí ẹ̀rọ-ayélujára kí ó ṣe àgbéjáde orin tirẹ̀ gan-an gan orin rẹ̀ yìí ló pe àkíyès...
babyboy av adindu victor tí wọ́n bí ní 14 march 1999 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ babyboy av jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó wá láti ìdílé olórin kan tí wọ́n ń pè ní 'the adindu's'
dammy krane oyindamola johnson emmanueltí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dammy krane jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti eléré
dekumzy derek osonwa tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dekumzy jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà atẹ dùrù àti akọrinsílẹ̀ ó ti ṣiṣẹ pẹ̀lú àwọn olórin bí i mr raw flavour bracket dr alban charly boy àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
dr alban alban uzoma nwapa tí wọ́n bí ní 26 august 1957 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dr alban jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ orílẹ̀-èdè sweden ó jẹ́ olórin àti agbórinjáde tó ní ilé-iṣẹ́ tirẹ̀ tó ń jẹ́ dr records
dj lambo olawunmi okerayi tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dj lambo jẹ́ dj ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2017 dj lambo wà lára àwọn dj tí wọ́n yàn láti ṣeré ní big brother nigeria
eddy wata eddy wata tí wọ́n bí ní 3 march 1976 jẹ́ olórin ilẹ̀ nàìjíríà
evi edna ogholi evi edna ogholi tí wọ́n bí ní 6 july 1966 jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó máa ń kọ orin reggae tó gbajúmọ̀ fún orin rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ happy birthday
fireboy dml adedamola oyinlola adefolahan tí wọ́n bí ní 5 february 1996 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ fireboy dml jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ ybnl nation èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tí olamide dá sílẹ̀
frank edwards frank ugochukwu edwards tí wọ́n bí ní 22 july 1989 jẹ́ olórin ẹ̀mi àti agbórinjáde ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó wá láti ipinle enugu
harrysong harrison tare okiri tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ harrysong jẹ́ olórin akọrinsílè àti eléré orin lóríṣiríṣi tó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tó kọ orin ẹ̀yẹ ìkẹyìn fún nelson mandela tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ the headies 2013
humblesmith ekenedirichukwu ijemba tí wọ́n bí ní may 14 1991 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ humblesmith jẹ́ olórin afropop ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó di gbajúmọ̀ ní ọdún 2015 lẹ́yì tó ṣàgbéjáde orin rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ osinachi
jamopyper jamiu damilare tajudeen tí wọ́n bí ní 25 october 1995 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ jamopyper jẹ́ olórin afrobeat ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2020 jamopyper tẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú zlatan ibile tó ni zanku records wọ́n yàn án fún ọ̀kan lára àwọn àmì-ẹ̀yẹthe headies 2020
àrùn jẹjẹrẹ ọmú cancer that originates in mammary glandsàrùn jẹjẹrẹ ọmú jẹ àrùn tó jẹyọ láti araàwọn ohun àsopọ tó wà nínú ọmú lára àwọn àmì àìsàn jẹjẹrẹ ní níní ééwo nínú ọmú ìyàtọ nínú ìrísí ọmú níní àwọ̀ tó dàbí èpo ọ̀sàn kí ìkókó máa kọ omi ọmú kí omi ọmú máa da láìfọ́mọ lọ́mú tí orí ọmú bá kojú sínú kí àwọ máa pọ ...
ounje omo food made especially for infants oúnjẹ ọmọ tàbí oúnjẹ ìkókó jẹ́ àwọn oúnjẹ tí wọ́n rọ̀ tí wọ́n lè ṣe é jẹ fún àwọn ìkókó yàtọ̀ sí omi ọmú tàbí àwọn oúnjẹ ọmọdé ìgbàlódé tí wọ́n ṣe fún jíjẹ ọmọ jòjòló tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju ọmọ oṣù mẹ́fà sí ọdún méjì lọ àwọn oúnjẹ wọ̀nyí máa ń wà lóríṣiríṣi pẹ̀lú adùn oríṣiríṣi...
infant infant tàbí ọmọ jòjòlọ́ jẹ́ ọmọdé tí kò tíì pé ọdún kan yorùbá ma ń pè wọ́n ní ọmọ titun tàbí ọmọ jòjòlọ́ ìrísí wọn èjìká àti ìbàdí ọmọdé ma ń sábà fẹ̀ ikùn wọn ma ń tóbi díẹ̀ orí ọmọdé orí ọmọdé ma ń sábà tóbi òkè orí wọnibi tí ọpọlọ wà sì ma ń tóbi ju ìyókù orí wọn lọ orí ọmọ aṣẹ̀ṣẹ̀bí sì ma ń tóbi tó 3336 cm ...
omi ọmú
omi omú
fífún ọmọ lọ́mú fífún ọmọ lọ́mú jẹ́ ọ̀nà tí à ń gbà fún ọmọ ọwọ́ ní ọmú tó ń ti igbáàyà obìnrin wá wàrà yìí le jẹ́ èyí tó wá láti ọmú tàbí èyí tí a fà sínú ike tí a sì ń fún ọmọ mu àjọ tó ń rí sí ètò ìlera who dámọ̀ràn pé kí ọmọ ọmú bẹ̀rẹ̀ láàárín wákàtí àkọ́kọ́ tí a bí ọmọ sáyé kí ó sì máa lọ bẹ́ẹ̀ títí tọ́mọ náà á fi...
world alliance for breastfeeding action àjọ world alliance for breastfeeding action waba jẹ́ akójọ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní agbáyé láti dẹ́kun ìdènà tí ó débá ifọ́mọlọ́mú kí wọ́n lè mú ìlọsíwájú bá ìpolówó fífún ọmọ lọ́mú akójọpọ̀ àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń lo àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi bíi jíjẹ́ ìyá ẹ̀tọ́ àwọn ònrà láti fẹsẹ...
omu sise release of milk from the mammary glands omú sísẹ̀ ṣe àpèjúwe ìtújáde wàrà láti àpò wàrà tí wọ́n ń pè ní mammary gland àti ìgbà tí ìyá ọmọ bá ń fún ìyá ní wàrà mu ní èyí jẹ́ ìlànà náà máa wáyé ní ọnà àrà ní ará ẹni tí ó bá jẹ́ obìnrin tàbí abo tí ó ti bàlágà ìlànà tí àwọn abo máa ń gbà fún àwọn ọmọ ní wàrà ní a...
àìsàn ikú òjijì ọmọdé sids sudden unexplained death of a child of less than one year of age sudden infant death syndrome sids tí ó túmọ̀ sí àrùn àìsàn ikú òjijì ọmọdé jẹ́ àrùn abàmì tí ó máa ń jásí ikú òjijì ọmọdé tí ọjọ́-orí kò ju ọdún kan lọ àwọn ikú òjijì báyìí ni a kì í mọ ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó fà wọ́n kódà bí àwọn onímọ̀ b...
ibimọ ọmọ bíbí tí a tún lè pè ní rírọbíìgbésè ìbímọ àti ìbímọ máa ń ṣelẹ̀ nígbà tí oyún bá ti parí tí omọ kan tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ máa ń wáyé nípa ìbímọ ojú ara tàbí ìbímo pẹ̀lú abẹ ni ọdun 2019 a rí 14011 mílíọ̀nù ìbí ènìyàn ní àgbáyé ní àwọn orílẹ̀-èdè́ tó ti ní ìdàgbàsókè ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n ń bí omọ máa ń wáyé ní i...
ikú ọmọ ọwó infant mortality death of children under the age of 1 ikú ọmọ ọwọ́ jẹ́ ikú tí ọmọ ọwọ́ máa ń kú kí ó tó tó ọmọ ọdún kan iye ìṣẹ̀lẹ̀ ikú ọmọ ọwọ́ nínú ètò ìkànìyàn ni à ń pè lédè òyìnbó ní infant mortality rate imr èyí ni iye àwọn ọmọ ọwọ́ ọjọ́ orí wọn kò tó ọdún kan tí wọ́n fi kú nínú ẹgbẹ̀rún kan àwọn ọmọ ...
bíbí ọmọ gboju obo vaginal delivery delivery through the vagina bíbí ọmọ gbojú obò vaginal delivery ni ọ̀nà ọmọ bíbí gba obò tí àwọn ẹranko afọ́mọlọ́mú àti ènìyàn máa ń bímọ wọ́n tún lè pè é ní ọmọ bíbí gbojú ara ó jẹ́ ọ̀nà ìgbàbímọ́ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ káàkiri àgbáyé l wọ́n gbà pé òun ló rọrùn julọ láti bímọ ju iṣẹ́-abẹ ...
oyun = ọmọ inú oyún foetus jẹ́ ọmọ tí a kò i tí bí tí o ńdàgbà gẹ́gẹ́bi oyún inú nínú ẹranko fún ènìyàn ìdàgbàsókè ọmọ inú oyún maa nbẹ̀rẹ̀ láti ọ́sẹ́ kẹsan lẹ́hìn íbásepọ̀ tí ọlè bá sọ ìpéle ìdàgbàsókè ọmọ inú oyún yoo bèrè sí tẹ̀síwájú títí di ìbímọ ídàgbàsóké ọmọ inú oyún ń ìtèsìwájú nígbà gbogbo láìsí ìyàtò laarin ...
ìkókó ìkókó tàbí ọmọ-ọwọ́ jẹ́ ọmọ tí ó kéré gan-an ti ẹ̀dá ènìyàn ọmọ ìkókó láti ọrọ latin infans tí ó túmọ̀ sí 'ọmọ ọwọ́' tàbí 'ọmọ' jẹ́ arọ́pò-ọ̀rọ̀ fún ọ̀rọ̀ tí ó wọ́pọ̀ ọmọ àwọn ọ̀rọ̀ náà lè tún ṣeé lò láti tọ́ka sí ọ̀dọ́ ọmọ tuntun jẹ́ lílò ọ̀pọ̀ ìkókó tí ó jẹ́ wákàtí nìkan ọjọ́ tàbí tí ó tó oṣù kan tí a bá fojú ì...
ogedegbe surname ogedegbe jo oruko idile naijiria iwonyi jo awon eniyan olokiki polu oruko idile awon itokasi yi ni a kukuru article jọwọ mu yi
ìrèké oníbùdó ìrèké oníbùdó jẹ́ ìwé kẹta tí d o fagunwa kọ tí ó sì sàtẹ̀jáde rẹ̀ ní ọdún 1949 láti ọwọ́ thomas nelson
estrogen estrojíínì tàbí oestrogen jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn hòmónù ìbálòpọ̀ tí tí wọ́n ń ṣisẹ́ ìdàgbà-sókè àti ìfètò sí ẹ̀yà ara ìbímọ lára àwọn obìnrin àti ìṣesí ìbálòpọ̀ lára obìnrin ìpín mẹ́rin ni a lè pín estrogen si látàrí ìṣesí àti iṣẹ́ wọn nínú ara obìnrin àwọn náà ni estrone e1 estradiol e2 àti estriol e3 estradiol tí...
kaduna museum kaduna museum jẹ́ museum ní ìlu kaduna nigeria wọ́n ṣí mùsíọ́mù náà ní ọdún 1975 ní ìfitọrẹ fún ìlú tí àwọn northern people's congress npc tẹ́lẹ̀ rí tí ìjọba ìpínlẹ̀ ti àárín gbùngbùn àríwá mùsíọ́mù kaduna náà kún fún àkójọpọ̀ àwọn ohun pàtàkì tí ó ní ṣe pẹ̀lú kíkọ́lé ohun ìṣẹ̀ǹbáyé àti àwọn oríṣiríṣi ohu...
kanta museum museum in nigeria mùsíọ́mu kanta jẹ́ mùsíọ́mu ní ìlú argungu ní orílẹ̀ èdè nigeria tó dẹ̀gbẹ́ kọjú sí ọjà wọ́n kọọ́ ní ọdún 1831 wọ́n sì sọọ́ lórúkọ lẹ́yìn muhammed kanta tí ó tẹ kebbi kingdom dó ní ọdún 1515 tí yakubu nabame sì kọọ́ ọba kebbi tí ó sì jẹ títí di 1942 tí àwọn aláwọ̀ funfun fi kọ́ ààfin tunt...
oron museum oron museum jẹ́ ilé tí àwọn ohun ìṣẹ̀mbáyé lọ́jọ̀ sí tí wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún 1958 tí ó wà ní ìlú oron ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n da ilé ìṣẹ̀mbáyé yí sílẹ̀ ní ọdún 1958 láti lè kò àwọn ohun ìṣẹ̀mbáyé àtijọ́ tí wọ́n tó ọgọ́rún mẹ́jọ tí wọ́n ṣe pàtàkì sí àṣà àti ìṣe àwọn ẹ̀yà oron tí wọ́n gbà wípé wọ́n wà lá...
the owo museum ilé ìṣẹ̀mbáyé ìlú ọ̀wọ̀ jẹ́ ilé ìṣẹ̀mbáyé ńlá kan tí ó wà ní ìlú ìlú ọ̀wọ̀ ní ìpínlẹ̀ òndó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n da ilé ìṣẹ̀mbáyé náà sílẹ̀ ní ọdún 1968 láti lè kó àwọn ohun ìṣẹ̀mbáyé ayé àtijọ́ tí kò sírú rẹ̀ mọ́ síbẹ̀ inú àgbàlá ààfin ọlọ́wọ̀ ni ilé ìṣẹ̀mbáyé yí wà tẹ́lẹ̀ ilé ìṣẹ̀mbáyé náà ní àwọ...
ulli beier museum ulli beier museum jẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣàfihàn àwòrán àti ilé-ìwé àwòrán ní òṣogbo nàìjíríà ó jẹ́ ìdásílẹ̀ nípasẹ̀ àwọn aṣàwòrán ulli beier àti susanne wenger lónìí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ aṣàfihàn àwòrán áfíríkà àsìkò ti ó ṣe pàtàkì tí ń gbàlejò iṣẹ́ àwọn aṣàwòrán tí ó ní òye àti àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dàgbà sínú iṣẹ́ lát...
esiẹ museum nigeria museum mùsíọ̀mù esiẹ jẹ́ mùsíọ̀mù ní ilẹ̀ esiẹ ní ìpínlẹ̀ kwara ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà mùsíọ̀mù yìí jẹ́ alàkọ́kọ́ tí wọ́n kọ́kọ́ dá sílẹ̀ ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà nígbà tí wọ́n ṣíi ní ọdún 1945 mùsíọ̀mù yìí fẹ̀kàn tẹ́lẹ̀ rí gba ọgọ́rùn-ún àwọn ère olókùúta itẹ́kù tí wọ́n fi dípò àwọn ènìyàn ìwúrí ni l...
national war museum umuahia
ile ọnọ kanta kanta mùsíọ́mù wà ní argungu ni ilú nàìjíríà tí ó kọ̀ ojú sì gbàgede ojú ọjà gangan ni ọdún 1831 ni a kọ́ kanta mùsíọ́mù wọ́n fún ilé náà ní orúkọ lẹ́hìn muhammed kanta láti lè máa ṣe ìrántí fún - un ọkùnrin yìí náà bákannáà ni ó dá ìjọba kebbi sílè ní ọdún 1515 yakubu nabame ní ó fi ilé náà lé lẹ̀ ó jé ọ...
mùsíọ́mù ti ìlú benin benin city national museum jẹ́ mùsíọ́mù ní ìlú benin ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó wà ní àárín ilu king's square mùsíọ́mù náà ní àwọn ohun-ọ̀ṣọ́ tí ó ṣe pàtàkì sí ìjọba benin bíi ìkòkò amọ̀ tàbí àwọn àwòrán tí wọ́n fi amọ̀ yà ́terracottaidẹàti àwọn irin tí a ti jó pọ̀ o tún ní àwọn àwòrán àtijọ́ tí ...
peter thomas king
kishore kumar kishore kumar g ni a bini ọjọ kẹfa dinlogun óṣu august ni ọdun 1974 jẹ óṣèrè lọkunrin ti ilẹ india ti a mọ si kishore
gidan makama museum kano gidan makama museum kano tàbí kano museum jẹ́ músíọ́ọ̀mù kan ní ipinle kano ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ilé yìí fìgbà kan jẹ́ ààfin ti sarakunan hausa èyí tó jẹ́ ọba àwọn hausa ti kano ṣáájú ààfin tó wà níkàlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ti gidan rumfa ní sẹ́ńtúrì kẹẹ̀ẹ́dógún músíọ́ọ̀mù yìí ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ...
españa
ososo ososo jẹ́ ìlú kan ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ akoko-ẹdó ní ìpínlẹ̀ ẹdó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ní ojú-ọjọ́ tó tutù púpọ̀ tí ó jọ ti ìlú jos pẹ̀lú ìwọ̀n gíga ti 1236 lókè ìpele òkun òkè tí ó ga jùlọ tóbi púpọ̀ tí wọ́n ń pè ní àpáta oruku àpejúwe ìlú náà jẹ́ ẹlẹ́yà mẹ́rin tí ń ṣe anni egbetua okhe àti ikpena pẹ̀lú iye...
koker olayiwola olabanji kokumo tí orúkọ ìnagijẹ rè ńj ẹ́ koker jẹ́ olórin afro-pop ti orílẹl-èdè nàìjíríà ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí koker ní ọjọ́ 30 oṣù may ní ọdún1993 ní ìpínlẹ̀ èkó
lyta babatunde rahim tí orúkọ ìnagijẹ̀ rẹ̀ ń jẹ́ lyta jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú ybnl nation ní ọdún 2018 àmọ́ ó kúrò lẹ́yìn èdè-àìyedè tó wáyé láàárín òun àti ẹni tó ní ilé-iṣẹ́ náà ìyẹn olamide ó ṣàgbéjáde àwo-orin olórin márùn-ún ep id ní ọdún 2019
may d akinmayokun awodumila tí wọ́n bí ní ọjọ́ 28 oṣù december ní ọdún 1984 tí wọ́n tún mọ̀ sí may d jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríà ó fìgbà kan wà ní ìtẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú rb àti square records èyi tí àwọn p-square
miraboi miracle kelechi chike tí wọ́n bí ní march 24 ọdún 1998 tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí miraboi jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrinkalẹ̀ òṣèrékùnrin onínúure àti oníṣòwò àwọn òbí rẹ̀ wá láti ipinle abia àmọ́ ìpínlẹ̀ èkó ló dàgbà sí níbi tí ó sì ti bẹ̀rẹl iṣẹ́ rẹ̀
mr 2kay abinye david jumbo tí wọ́n bí ní february 11 ọdún 1988 tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí mr 2kay jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó fìgbà kan tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú grafton entertainment àmọ́ ó kúrò ní ọdún 2018 láti lọ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀ tó pè ní better life entertainment
niyola eniola akinbo tí wọ́n bí ọjọ́ 9 oṣù december ọdún 1985 tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọl sí niyola jẹ́ olórin orílè-èdè nàìjíríà
nonso amadi chinonso obinna amadi tí wọ́n bí ní september 1 ọdún 1995 jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrinkalẹ̀ àti agbórinjáde ó jẹ́ olórin tó kọ́ ara rẹ̀ níṣẹ́ orin kíkọ àti bí wọ́n ṣe ń gbórinjáde ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ yìí nígbà tí ó wá ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti covenant university níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa
nonso bassey chukwunonso anozuma bassey iwuchukwu tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí nonzo bassey tó fìgbà kan jẹ́ nonso bassey jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrinkalẹ̀ òṣèrékùnrini àti módẹ́ẹ̀lì
orezi esegine allen tí wọ́n bí ní 28 march 1986 tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí orezi jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó wá láti ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ó di gbajúgbajà nígbà tó kọ orin tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ rihanna ní ọdún 2013
orits williki orits wiliki jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè naijiria tó máá ń kọ orin reggae ó dí gbajúmọ̀ nígbà tí ó gbé orin kan jáde ní ọdún 1989 tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ tribulation wiliki tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ musical copyright society of nigeria èyí tó jẹ́ ẹgbẹ́ olórogún ti copyright society of nigeria
orlando julius orlando julius aremu olusanya ekemode tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí orlando julius tàbí orlando julius ekemode tí wọ́n bí ní 22 september 1943 tó sì ṣaláìsí ní14 april 2022 jẹ́ olórin afunfèrè olórí-ẹgbẹ́-orin àti akọrinkalẹ̀ tó ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú afrobeat music
osita osadebe chief stephen osita osadebe tí wọ́n bí ní march 17 1936 tó sì ṣaláìsí ní may 11 2007 tí ọ̀pọ̀ ènìuàn mọ̀ sí osita osadebe jẹ́ olórin tó wá láti atani ọ̀kan lára àwọn orin rẹ̀ tó gbajúgbajà tó kọ ní ọdún 1984 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ osondi owendi èyí tó fi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èd...
fartuun adan fartuun abdisalaan adan jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn ti ìlú somalia òun ni adarí àgbà fún elman peace and human rights centre ìgbésí ayé rẹ̀ adan dàgbà sí ìlú somalia ó fẹ́ elman ali ahmed tó jẹ́ oníṣòwò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn tó ń rí sétò àlàáfíà wọ́n sì jọ bí ọmọ mẹ́rin
adan mohammed adan abdulla mohammed jẹ́ gbajúgbajà òṣìṣẹ́ ilé-ìfowópamọ́ ti ìlú kenya àti oníṣòwò ó fìgbà kan sìn gẹ́gẹ́ bí i adarí àgbà ti barclays bank ní ìwọ̀-oòrùn ti àti west africa
adán augusto lópez hernández adán augusto lópez hernández tí wọ́n bí ní september 24 1963 jẹ́ olóṣèlú ilẹ̀ mexico agbẹjọ́rò
adán jodorowsky adán jodorowsky or adanowsky tí wọ́n bí ní 29 october 1979 jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè mexico tó tan mọ́ ìlú fránsì ó sì tún jẹ́ òṣèrékùnrin àti adarí-eré
edna adan ismail edna adan ismail tí wọ́n bí ní born 8 september 1937 jẹ́ agbẹ̀bí ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn ó sí tún jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ mínísítà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè fún orílẹ̀-èdè somalia láti ọdún 2003 wọ 2006 òun sì ni ààrẹ ẹgbẹ́ victims of torture ìbẹ̀rẹ̀pẹlpẹ̀ ayé rẹ̀ ìlú hargeisa ni wọ́n bí ismail sí ní 8 septem...
mahathir mohamad
raymond ablack raymond ablack tí wọ́n bí ní november 12 1989 jẹ́ òṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè canada ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2000 gẹ́gẹ́ bí i òṣèrémọdé lóri ìtàgé tó sì ṣe ẹ̀dá-ìtàn young simba nínú the lion king ní princess of wales theatre
james acaster james william acaster tí wọ́n bí ní 9 january 1985 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ti ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì
kev adams kev adams tàbí kev' adams tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ kevin smadja 1 july 1991 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ilẹ̀ fránsì òṣèrékùnrín àti aṣàgbéjáde fíìmù
pamela adlon pamela fionna adlon tí wọ́n bí ní july 6 1966 jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílẹ̀ èdè america ó gbajúgbajà fún lílo ohùn rẹ̀ láti fi ṣe ẹ̀dá-ìtàn bobby hill nínú fíìmù king of the hill 19972010
steve agee steven douglas agee tí wọ́n bí ní february 26 1969 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀ èdè america òǹkọ̀wé àti olórin ó tún máa ń tẹ dùrù pẹ̀lú ẹgbẹ́ olórin lóríṣiríṣi ní ọdún 1990 ó sì ti fìgbà kan ṣẹrẹ́ pọ̀ pẹ̀lú brendon small
alex agnew alex agnew tí wọ́n bí ní 22 december 1972 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ti ilẹ̀ belgium àti olórin
rubén aguirre rubén aguirre fuentes tí wọ́n bí ní 15 june 1934 tó sì ṣaláìsí ní 17 june 2016 fìgbà kan jẹ́ oṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín ti ilẹ̀ mexico
dan ahdoot dan kamyar ahdoot jẹ́ oṣèrékùnrin òǹkọ̀wé àti apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀ èdè america