raw_text
stringlengths
2
128k
omo-love branch nigerian footballer omo-love branch tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 1974 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá bìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó máa ń gbá bọ́ọ̀lù ní àyè àbò-ilé fún ọkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin nigeria ó wà lára ikọ̀ àkọ́kọ́ àwọn obìnrin tí wọ́n ṣojú nàìjíríà nínú ìdíje 1991 fifa wom...
hafsat abiola nigerian human rights civil rights and democracy activist hafsat olaronke abiola-costello tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọkàn lé lógún oṣù kéje ọdún 1974 ní ìlú èkó ó jẹ́ àjàfẹ́tọ̀ọ́ ẹ̀tọ́ ọmọ nàìjíríà àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú àjàfẹ́tọ̀ọ́ ìjọba ara wa àti olùdásílẹ̀ kudirat initiative for democracy kind èyí tí ó ń wá láti f...
abiola dosunmu oloye abiola dosunmu ti a mo tele si dosunmu-elegbede-fernandez a bi ni july 29 1947 je onisowo ni orile ede naijiria o je alafeati o nise ibile ni afikuno di erelu kuti eekerin ti ilu eko
jessica oyelowo jessica oyelowo née watson ti a bi ni 1978 je osere ati okorin ti britain iberepepe aye oruko ti won so ni jessica watson ni ipswich o si dagba si suffolk ni england o losi ile iwe alakobere ti woodbridge school nigba ti o wa ni kekere o si je omo egbe national youth music theatre ise ni odun 2006 oun l...
tanimowo ogunlesi nigerian activist tanimowo ogunlesi 1908-2002 jẹ́ ajàfẹ́ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ilẹ̀ nàìjíríà ó tún jẹ́ adarí women's improvement league ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí tó ń já à fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin àti ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ national council of women societies tí ń ṣe aṣáájú iléeṣẹ́ ajàfẹ́ẹ̀tọ́ àwọn ob...
kemi omololu-olunloyo nigerian journalist and activistkemi omololu-olunloyo olukemi omololu-olunloyo tí a bí ní ọjọ́ kẹfà osù kẹjọ1964 jè akọ̀ròyìn ajàfẹ́tọ̀ọ́ọmọnìyàn àti gbajúmọ̀ lórí ìkànnì ayélujára ní nàìjíríà ó jẹ́ gbajúmọ̀ ní orí ìkànnì ayélujára ní nàìjírìà pàápàá jùlọ fún síse àríyànjiyàn lóri àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ...
faith abiola oyedepo faith abiola oyedepo born febuary 5 1958 is a nigerian preacher she is the wife of david olaniyi oyedepo who is a christian author businessman architect the founder and presiding bishop of living faith church worldwide and also the chancellor of covenant university and landmark university respectiv...
alimotu pelewura oloye alimotu pelewura 18651951 jẹ onísòwò naijiria kàn tó jẹ adarí ẹgbẹ awon obinrin ti oja eko egbé agbawi obìnrin tí o jẹ onísòwò ní eko o tún jẹ ẹlẹgbẹ òṣèlú pàtàkì ti herbert macaulay ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ ìlú eko ní wón tí bí pelewura si idile nla kan ó jẹ́ àgbà ti àwọn ọmọ méjì tí ìyá rẹ̀ bí ìya rẹ...
charlotte obasa charlotte olajumoke ọbasá tí orúkọ ìbí rẹ̀ ń jẹ́ blaize ọjọ́ keje oṣù kìíní ọdún 1874 sí ọjọ́ ẹ̀tà lè lógún oṣù kẹwàá ọdún 1953 jẹ́ ẹni àrà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti onínúureó jẹ́ ọmọbìnrin oníṣòwò rb blaize àti ìyàwó oníṣègùn orisadipe obasa ayé rẹ̀ sàró obasá kan ni wọ́n bí gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan lára àw...
chief temitope ajayi nigerian business consultant amina temitope ajayi aka mama diaspora jẹ́ ọmọ nàìjíríà tí ó ń gbé ní us àjùmọ̀sọ̀rọ̀ òwò tí ó ń kọ́ ìṣìrò on tàjà àwùjọ àti alákòóso aláápọn àgbègbè tèmítọ́pẹ́ àjàyí fi ìgbà kan jẹ́ ààrẹ gbogbo nigerian american congress anac akitiyan rẹ̀ àti itẹ̀síwájú àgbàwí lórí í n...
yemisi ransome-kuti yemisi ransome-kuti ni ó jẹ́ ọmọ kan ṣoṣo ardbìmrin azariah olusegun ransome-kuti mbe tí wọ́n yàn sípò as ọ̀gá agbà onímọ̀ ìpoògùn fún orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 1956 tí ó sì ṣiṣẹ́ títí di ó fi fẹ̀yìn tì ní ọdún 1951 member of the most excellent order of the british empire láti ọwọ́ king george vi ...
omo-oba adenrele ademola princess adenrele ademola tàbí omo-oba adenrele ademola tí a bí ní ọdún 1916 jẹ́ ọmọ-ọba kan ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti òṣìṣẹ́ ìlera ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè gẹ́gẹ́ bíi nọ́ọ̀sì ní ìlú london ní ọdún 1930 ó sì ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ lọ nígbà ogun àgbáyé kejì wọ́n fi ṣe orí-ọ̀rọ̀ fún fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ...
kemi badenoch olúkẹ́mi olúfúntọ́ badenoch /ˈbeɪdnɒk/ -nok nee adegoke born 2 january 1980 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì ó jẹ́ ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ní ẹkùn ìdìbò saffron walden láti ọdún 2017 títí di àkókò yìí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú conservative party ó ti fìgbà kan jẹ́ mínísítà kéréje fún ìjọb...
adenike oladosu adenike oladosu tí wọ́n bí ní 1994 jẹ́ olùgbèjà fún agbègbè àláìléwu fún àwọn ènìyàn àwùjọ ó sì tún jẹ́ olùgbèrò fún ìdaṣẹ́sílè ilé-ẹ̀kọ́ fún ojú-ọjọ́ tó tẹ́rùn ní oríléédè nàìjíríà ó tún ṣàfihàn ìṣe ojú-ọjọ́ àìléwu ní àwọn àpèjọ ilẹ̀ òkèèrè tí un climate change conference world economic forum àti eleva...
fila abeti aja abetí ajá túmọ̀ sí bí etí ajá ó jẹ́ orísun yorùbá ìlú ìbàdàn abetí ajá yìí ni fìlà tí a fi aṣọ òkè tàbí aṣọ àdìre rán ó jẹ́ apá kan ti aṣọ ọkọ ìyàwó máa ń wọ̀ nígbà ayẹyẹ ìgbéyàwó tàbí tí ọba ẹni ọlọ́rọ̀ àti ẹni oyè máa ń wọ̀ aṣọ òkè tí a fi ṣe fìlà abetí ajá yìí tún lè túmọ̀ sí aṣọ ipò gíga ó ní àgbékọj...
nigeria ministry of education ilé-iṣẹ́ àpapọ̀ ẹ̀kọ́ tí wọ́n máa ń pè ní federal ministry of education jẹ́ apá kan ti àwọn ilé-iṣẹ́ àpapọ̀ naijiria federal ministries of nigeria tí ó ń ṣe ìtọ́sọ́nà ètó-ẹ̀kọ́ ní nàìjíríà ó wà ní block 5a 8th floor federal secretariat complex shehu shagari way central area pmb 146 garki a...
àhámọ́
ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè linguistics ni ìmọ̀ nípa àbùdá èdè tí ọmọ ẹ̀dá ènìyàn n sọ tàbí sàmì sign àwọn onímọ̀ ẹ̀dá-èdè máa ń ṣe àgbéyẹ̀wò bi èdè ṣe nííṣe pẹ̀lú ìròrí àti láàkàyè àti bí àwọn eniyan ṣe ń sàmúlò èdè láàrin àwùjọ
shina peller shina abiola peller ojoibi 14 may 1976 je omo orile-ede naijiria otaja oloselu onise ile ise ati asòfin ni ilé ìgbìmọ̀ asòfin 9th o jẹ alaga ati oludari agba ti aquila group of companies ati club quilox shina peller ni o ni awọn akọle ijoye mejeeji ti ayedero ti ilẹ yoruba ati akinrogun ti ilẹ epe lagos ni...
hope waddell training institute colonial school in calabar cross river state nigeria hope waddell training institution howad jẹ́ ilé-ìwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú calabar ní ìpínlẹ̀ cross river lórílẹ̀-èdè nigeria àwọn àlùfáà ìjọ kìrìsìtẹ́nì ti united presbyterian church of scotland ni wọ́n dá a sílẹ̀ lọ́dún 1895 tí...
alakuko alakuko je agbegbe kan ni ipinle ilu ekoilu alakuko wa labe isakoso ojoroko lcdaeleyi ti arakunrin hammed tijani je olusakoso ati oludari agbegbe naa
muhammed ali mungeri
ahmad ali saharanpuri aḥmad ali saharānpuri ọdún 1810 sí ọjọ́ ẹẹ́ta-dín-lógún oṣù kẹrin ọdún 1880 jẹ́ ọ̀mọ̀wé hadith ní ilẹ̀ india tí ó kó ipa pàtàkì nínú títè jáde lítíréṣọ̀ hadīth ní india ó wà láàrin àwọn olùkọ́ àkọ́kọ́ tí mazahir uloom àti pé ìgbàgbogbo ni a kàá bí olùdásílẹ̀ fún àwọn ìlọwọ́sí rẹ̀ sí ìdàgbàsókè ilé...
fola evans-akingbola fola evans-akingbola tí a bí ní ọjọ́ ẹ̀rìn-dín-lọ́gọ́ta ọdún 1994 jẹ́ òṣèré aláwọ̀ funfun ti british ó ṣe maddie bishop ní freeform series siren ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ní ìlú london ni wọ́n bí evans-akingbola sí ìyá onímọ̀-ìjìnlẹ̀ ará ìlú gẹ̀ẹ́sì kan dókítà gillian evans àti bàbá rẹ̀ akọrin ilẹ̀ nàì...
mọfọ́lọ́jì mọfọloji jẹ ẹka ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè linguistics ti o n ṣe agbeyẹwo ihun ọrọ ati awọn abuda rẹ mọfọlọji a maa ṣe itupalẹ ọrọ si awọn ẹyọ onitumọ to kere ju lọ ti a n pe ni mọfiimu
fola-evans akingbola
joy olasunmibo ogunmakin joy olasunmibo ogunmakin tí á bí ni 14 september 1980 tí a mọ̀ sí ayọ jẹ̀ ọ̀kọrin orílé èdè german ẹnití tí ó ma ń kọ orin silẹ àti òṣèré ó lo èdè yorùbá láti tù orúkọ rẹ̀ tí ṣe joy ni ede gẹ̀ẹ́sì sí èdè yorùbá tíì ṣe ayọ̀ èyí tí ó jẹ́ orúkọ àbísọ rẹ̀ debut album rẹ̀ tí ṣe joyful jáde ní ọdún 2...
iya gbonkan margaret bandele olayinka tí a bí ní ọjọ́ ẹ̀rìn-lé-lẹ́wàá oṣù kẹsán ọdún 1958 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ìyá gbónkán jẹ́ òṣèré òníwòsàn ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà tí ó jẹ́ olókìkí púpọ̀ jùlọ fún ìrísí ojú ẹ̀rù rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ìyá gbónkán sábà máa ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àjẹ́ búburú ní eré jara ti yorùbá èyí fi hàn gedegbe nípas...
yetide badaki nigerian-born american actressyetide badaki a bi ni ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1981 ó jẹ́ òṣèré ní ìlú amẹ́ríkà tó sì jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ nàìjíríà ó sì jẹ́ ẹni tí amọ̀ sí ẹni tó má ń ṣerè bilquis lóri sírìsì starz american gods ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé a bí badaki sí ìlú ìbàdàn nàìjíríà kó tó lọ sí englan...
aisha abimbola aisha abimbola tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejìlá ọdún 1970 tí ó sì kú ní ọjọ́ karùn-úndínlógún oṣù kàrún ọdún 2018 jẹ́ òṣèrébìnrin ti ìlẹ̀ nàìjíríà ó sì tún jẹ́ òṣèré yorùbá tó gbayì
école nationale de l’aviation civile école nationale de l’aviation civile je yunifasiti ni ilu toulouse ni fránsì
joy olasunmibo ogunmakim
bím̀bọ́ ọ̀ṣìn
bímbọ́ manuel
péjú ògúnmọ́lá
ṣadé bádérìnwá
kúnlé afod
jìmí ṣólàńkẹ́
dúró ládipọ̀
ògèdèngbé agbógungbórò
erik ten hag erik ten hag dutch ̍ˈeːrɪk tən ɦɑx </img> ti a bi ni ọjọ keji osu keji odun 1970 jẹ olukọni alamọdaju bọọlu ti dutch ati agbabọọlu tẹlẹ ti o tun jẹ oluṣakoso lọwọlọwọ ti ẹgbẹ agbabọọlu manchester united ni premier league gẹgẹbi ẹrọ orin kan ten hag gba bọọlu ni owo aarin-lehin ni liigi dutch fun ọdun metal...
doyin abiola dr doyin abiola doyinsola hamidat abiola nee aboaba ti jẹ́ aṣàkóso olùdarí àti aṣàtẹ̀jáde ìwé ìròyìn national concord newspaper òun ni obìnrin nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ olóòtú ìwé ìròyìn daily times of nigeria| nigerian daily ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ dr doyin abiola kẹ́kọ̀ọ́ ní yunifásitì ti ìbàdàn nàìjíríà níbi t...
yewande omotoso yewande omotoso tí wọ́n bí ní 1980 jẹ́ òǹkọ̀wé ìwé eré-onítàn tí ó jẹ́ olùgbé south african ayàwòrán ilé àti a-ṣe-ọ̀ṣọ́ tí wọ́n bí ní barbados tí ó sì dàgbà ní nàìjíríà ó jẹ́ ọmọbìnrin òǹkọ̀wé nàìjíríà kole omotoso àti arábìnrin aṣàgbéjáde fíìmù akin omotoso ó ń gbé ní johannesburg àwọn ìwé eré-onítàn r...
mahmud hasan deobandi mahmud hasan deobandi tí a tún mọ̀ sí shaykh al-hind 18511920 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí india àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ìrìn òmìnira india tí ó pẹ̀lú dá yunifásítì jamia millia islamia sílẹ̀ àti dá silk letter movement fún òmìnira india ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ àkọ́kọ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ ẹ̀sìn darul uloom deoband ...
muhammad adil khan muḥammad adil khan tàbí adil khān 1957 10 october 2020 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè pakistan òun sì ni ọ̀gá ilé-ìwé jamia farooqia wọ́n mọ̀ ọ́n gẹ́gẹ́ bíi gbajúgbajà onímọ̀ mùsùlùmí ní pakistan khan jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ gboyè ti ilé-ìwé jamia farooqia àti university of karachi ó sì kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ n...
ebrahim desai south african muslim scholar and jurist 19632021 ebrahim desai ọjọ́ ẹ̀rìn-dín-lógún oṣù kìíní ọdún 1963 sí ọjọ́ márùn-ún dín lógún oṣù kéje ọdún 2021 jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀sìn mùsùlùmí orílẹ̀-èdè south africa àti olófin tí ó ṣe ìdásílẹ̀ darul iftaa mahmudiyyah ojú askimam fatawa àti pé ó jẹ́ olùkọ́ àgbà ti...
suzanne iroche suzanne olufunke iroche tàbí suzanne olufunke soboyejo-iroche jẹ́ òṣìṣẹ́ báǹkí ní orílé èdè nàìjíríà èyí tí ó ń darí finbank tí orílé èdè nàìjíríà ìgbé ayé iroche lọ sí ilé ìwé gírámà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ queen's college èyí tí ó wà ní ìpínlè èkó àti fásitì tí amọ̀ sí unilag lẹyìn èyí ní ọ lọ sí kellogg sc...
amy jadesimi nigerian businesswoman amy jadesimi ibí 1976 jẹ́ oníṣòwò orílé èdè nàìjíríà àti adarí àgbà fún ilé iṣé deep offshore logistics base tí ó wà ní ìpínlè èkó ladol èyí tí bí jẹ́ ilé iṣé aládání tí ó ń ṣe iṣé logistics àti engineering ní ogbà tí wón mọ̀ sí port of lagos
tosin oshinowo tosin oshinowo jẹ́ oníṣòwò òṣèré ayàwòrán-ilé orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwòrán ilé-ìtajà ńlá ti maryland to yà ni ó sọ ọ́ di ìlúmọ̀ọ́ká akẹ́kọ̀ọ́ gboyè ilé-ìwé kingston college ìlú london ni tosin ó sì tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni bartlett school of architecture ọ̀pọ̀ iṣẹ́ ni tosin ti ṣe ni ilẹ̀ yìí àti ní òkè-...
olawunmi banjo olawunmi banjo tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógbọ̀n oṣù keje ọdun 1985 jẹ́ olùyàwòrán ọmọ orílè-èdè nàìjíríà ìpínlè èkó ni ó ń gbé tí ó sì ti ń ya àwórán ayé rè a bí banjo sí ìpínlè ogun nàìjirià o ka ìwé ní yunifásitì ti pan africa àwọn nǹkan tí ó fi ń yàwòrán ni èèdú àti akiriliki lórí kanfasi ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwò...
muhammed ali mungeri
faizul waheed faizul waheed tí wọ́n tún mọ̀ sí faizul waheed qāsmī wọ́n bí ní ọdún 1964 tí ó sì fi ayé lẹ̀ ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹfà ọdún 2021 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀sìn ìsìláàmù onímọ̀ òfin ẹ̀sìn ìsìláàmù àti onímọ̀ ìtumọ̀ kòrání jammu àti kashmir tí ó jẹ́ olórí àwọn múfútí fún markaz-ul-ma'arif ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ fún ẹ̀sìn ìsì...
tobi amusan olúwatóbilọ́ba ayọ̀midé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tóbi amúsàn tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1997 jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ ehoro asáré-díje pàápàá jù lọ eré orí pápá oníwọ̀n ọlọ́gọ́rùn mítà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ó borí nínú ìdíje 2022 world athletics championships nínú eré-ìjẹ oníwọ̀n ọlọ́gọ́rùnún m...
sonya clark sonya clark tí a bí ní washington dc ni odun 1967 jé oluya/oluse aworan ní orílè-èdè amerika orisirisi nkan ni sonya n fi se àwòrán àwon nkan bi òwú aso irun ènìyàn àti béèbéè lo baba clark jé dokita tí óun toju wèrè ní trinidad ìyá clark sì jé noosi láti jamaica àwon ènìyàn nínú idile clark ni o jé orisun ...
nkechi blessing sunday nigerian actress nkechi blessing sunday a bíi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1989 jẹ́ olùgbé ilẹ̀ amẹ́ríkà òṣèré orílẹ̀-èdè nàìjíríà olóòtú fíìmù adarí fíìmù àti screenwriter wọ́n tọ dàgbà ní surulere ní ìpínlẹ̀ èkó ó ṣàgbéjáde fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ omoege lekki ní ọdún 2015 tí òun tìkalára rẹ̀ jẹ́ ak...
amu jadesinmi
dj cuppy florence ifeoluwa otedola á bí ní ójó kókànlá osù kòkànlá ódún 1992 tí á mọ̀ ní ọ̀jọ̀gbọ̀n sí dj cuppy tàbì cuppy nìkán ó jẹ́ disc jockey nàíjíríà àtí ólùpílẹ́ṣẹ́ ó jé ómọ́bínrín ónísòwò nàíjíríà femi otedola ó dágbà ní ìlù èkò ó sí lọ́ sí ìlù lọndọn ní ọ́mọ́ ọ́dún kétàlà ígbésí áyé ìbẹ̀rẹ̀ àtì ẹ̀kọ̀ cuppy gbé...
temie giwa-tunbosun temie giwa-tubosun wọ́n bí olúwalòní olámìídé gíwá ní oṣù kejìlá ọdún 1985 ó jẹ́ alàkóso ìlera nàìjíríà-amẹ́ríkà òun sì ni olùdásílẹ̀ lifebank tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ń jẹ́ one percent project ilé-iṣẹ́ tó wà ní nàìjíríà tó ń ṣiṣẹ́ lórí láti fi ẹ̀jẹ̀ tó dára láti ara ẹnìkan sí ẹlòmíràn ní ìlú
plants in space
peju alatise peju alatise jẹ ayàwòrán ilẹ̀ nàìjíríà akẹ́wì òǹkọ̀wé àti ọ̀kan lára àwọn òṣìṣẹ́ ni national museum of african art tí ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà smithsonian institution ọdún 1975 ni wọ́n bí alatise sí ìdílé mùsùlùmí òdodo ní ìlú èkó ilé-ìwé ladoke akintola university ní ìpínlẹ̀ oyo orílẹ̀-èdè nàìjíríà lẹ́yìn ìw...
ibidun ighodalo ibidunni ighodalo oṣù keje ọdún 1980 sí ọjọ́ kẹrìnlá ọdún 2020 jẹ́ yèyé ẹwà kan ti tẹ́lẹ̀ onímọ̀ ìṣàkóso ìṣẹ̀lẹ̀ onínúure pẹ̀lú olùṣọ àgùntàn ilé ìjọsìn trinity house ní ìlú èkó nàìjíríà ó jẹ́ olùdásílẹ̀ elizabeth r ilé-iṣé ìbátan gbogbo gbò àti ìṣẹ̀lẹ̀ pẹ̀lú ibidunni ighodalo foundation agbárí tí kìí ṣ...
stella fakiyesi stella fakiyesi ti a bi c 1971 jẹ oluyaworan ti o ṣẹda lorilẹ-ede naijiria sinima ati oluyaworan awọn iṣẹ fakiyesi ni fọtoyiya ati aworan wiwo ti jẹ ifihan ni ọpọlọpọ awọn ifihan agbaye igbesiaye wan bi fakiyesi ni naijiria o kọ ẹkọ fọtoyiya ni ile-ẹkọ giga ti ile-ẹkọ giga ti art amp design lati 1993 si...
oloye obafemi awolowo abí olóyè obáfémi jeremáyà oyèníyì awólówò ni ojó kefà osù keta odun 1909 o si kú ni ojó kesan osù karun odun 1987 6 march 1909 9 may 1987 o jé òkan nínú àwon ògunna-gbòngbò tí o ja fún òmìnira orílé-èdè naijeriya a bíi ni ilu ìkénné-rémo ní ìpínlè ogun òun nï kna ni omo okùnrin ninu gbogbo awon o...
peteru iii ti portugal peteru iii lisbon 1717 queluz 1786 ti a pe ni capacidónio sacristão ati edificador jẹ ọba consort ti portugal ati algarves lati ọdun 1777 titi di iku rẹ o jẹ ọmọ ọba joan v ati iyawo rẹ archduchess maria ana ti austria nitorina o jẹ aburo ti ọba josefu i ati aburo maria d peteru ko kopa ninu iṣel...
akojo awon akorin naijiria none eyi je akojo awon akorin naijiria
2face innocent ujah idibia ti wo bi 18 osu kesan odun 1975 ti a mo si 2baba je akorin naijiria
ana mena rojas ana mena ojoibi 25 february 1997 estepona spéìn je olorin omo ile spéìn
amina j mohammed amina jane mohammed tí a bí ní 27 june 1971 jé olósèlú omo orílè-èdè nàìjíríà àti orílè-èdè britain òun ígbákejì akowe fun igbimọ gbogboogbo ti orilẹ-ede agbayeunited nations lowolowo laarin odun 2015 sí 2016 òun ni lo jé minisita nàìjíríà fun ètó adugbo ìpìlè àti èkó rè a bí amina jane mohammed ni ojo...
do fagunwa
fifi ejindu nigerian architect ọmọọbabìnrin fifi ekanem ejindu jẹ́ ayàwòrán-ilé oníṣòwò obìnrin àti onínúure ará ilẹ̀ nàìjíríà a bí i ní ìlú ìbàdàn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ ọmọbìnrin ọba james ekpo bassey ti ìlú cobham ní calabar ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìtàn ìgbésí-ayé fifi jẹ́ ọmọ ọmọọmọ james ekpo bassey efik ...
ibukun oluwa abiodun awosika ìbùkúnolúwa abíọ́dún awóṣìkà bílíkísù abíọ́dún motúnráyọ̀ ọmọ́bọ́láńlé adékọ́lá tí wọ́n bí ní 24 oṣù kọkànlá 1962 jẹ́ obìnrin oníṣòwò nàìjíríà abáni-sọ̀rọ̀-ìyànjú àti òǹkọ̀wé ó jẹ́ alága tẹ́lẹ̀rí first bank of nigeria ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí-ayé àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí i gẹ́gẹ́ bí i ọmọ kẹta nínú ọmọ méje...
asake ahmed ololade tí wọ́n bí ni ojó kankànlá oṣú kẹfà ọdún 1995 tí orúkọ ìnágìjẹ rẹ̀ ǹjè asake jẹ́ olórin afrobeats láti orílẹ́ èdè nàìjíríà ójẹ́ olórin lábẹ́ àkóso ybnl nation iṣẹ́ asake kẹ́kọ̀ọ́ theatre performing arts ní obafemi awolowo university ile-ife osun state iṣẹ orin rẹ di gbajumọ ni ọdun 2020 nigbati o se...
olaoluwa abagun nigerian lawyer and women's rights activistolaoluwa abagun jẹ́ agbẹjọ́rò nàìjíríà àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ obìnrin ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí-ayé àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí abagun ní èkó ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní 2008 kúrò ní queens’ college lagos níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ “outstanding service to college life award” gẹ́gẹ́ bí igbákejì olór...
uduak isong uduak isong oguamanam jẹ́ akọ̀tàn nàìjíríà nollywood aṣàgbéjáde àti oníṣòwò tí ó ń gbé ní èkó nàìjíríà ó gbajúmọ̀ fún àwọn fíìmù adẹ́rìn-ín-pòṣónú okon lagos 2011 àti àtẹ̀lé rẹ̀ okon goes to school 2013 lost in london 2017 àti desperate housegirls 2015 falling fíìmù 2015 jẹ́ fíìmù isong oguamanam àkọ́kọ́ lá...
roseline òṣípìtàn yeye oba ti ìlú itori kingdom oloorì roseline omolará osípìtàn jẹ́ ọmọọba ilé yorùbá ó sí tún jẹ́ oníṣòwò orílé èdè nàìjíríà ọ tí jẹ ààrẹ àti aláàga rí fún ilé iṣé independent petroleum marketers association ti egbé àwọn obìnrin ó sí jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé iṣé royal oil and gas òun náà sini yèyé ọba fún ì...
ọlájùmọ̀kẹ́ adénọ́wọ̀
yewande omotoso
abísòyè àjàyí akínfọlárìn
ẹfúnṣetán aníwúrà
bọ́láńlé nínálowó
bọ́láńlé awẹ́
kẹ́hìndé ọlọ́runyọmí
àlàbá lawson
àlàbà jonathan
àbíbátù mọ́gàjí
dúpẹ́ jáyésinmi
tósìn jẹ́gẹ́dẹ́
rafael orozco maestre rafael josé orozco maestre march 24 1954 june 11 1992 jẹ́ olórin ara kòlómbìà o jẹ ọkan ninu awọn aṣoju ti o dara julọ ti orin colombian ati pẹlu israeli romero o ṣẹda ẹgbẹ orin el binomio de oro de américa
université paris-sud yunifásítì ìlú paris-sud tabi yunifasiti paris-sud jẹ ile-ẹkọ giga faranse ti a ṣẹda ni oṣu kini ọjọ 1 ọdun 1971 o parẹ ni oṣu kini ọjọ 1 ọdun 2020 ni ojurere ti yunifásítì ìlú paris-saclay ti o tẹle atẹjade ni iwe akọọlẹ iṣeduro ti aṣẹ ti o ṣẹda ile-ẹkọ giga tuntun ni oṣu kọkanla ọjọ 5 ọdun 2019
sean lock sean lock 22 kẹrin 1963 - 16 oṣu kẹjọ 2021 jẹ apanilẹrin ati oṣere gẹẹsi kan o bẹrẹ iṣẹ awada rẹ gẹgẹbi apanilẹrin imurasilẹ ati ni ọdun 2000 o gba aami eye awada ilu gẹẹsi ni ẹka apanilẹrin live ti o dara julọ ati pe o tun yan fun aami eye perrier comedy o jẹ olori ẹgbẹ lori ifihan nronu awada ikanni 4 8 ​​n...
université paris-diderot yunifásítì ìlú paris-diderot tabi yunifasiti paris-diderot jẹ ile-ẹkọ giga faranse ti a ṣẹda ni oṣu kini ọjọ 1 ọdun 1971 o parẹ ni oṣu kini ọjọ 1 ọdun 2020 ni ojurere ti université paris cité ti o tẹle atẹjade ni iwe akọọlẹ iṣeduro ti aṣẹ ti o ṣẹda ile-ẹkọ giga tuntun ni oṣu kẹta ọjọ 20 ọdun 20...
akínwùnmí ambọ̀dé
feminism
ìṣègbèfábo
ìjà fẹ́tọ̀ọ́ obìnrin ìṣègbèfábo feminism
eka soup eka soup eka soup tí a tún mọ̀ sí ekuku jẹ́ oúnjẹ ẹ̀yà méta ní apá ìla-oòrùn ilè nàìjíríà èkùrọ́ ẹ̀pà sísun àti kóró benne tí a gún ni a fi máa ń se eka soup fufu ni ó dùn jù láti fi jẹ́ orísun ọbẹ̀ náà wọ́pọ̀ láàrín àwọn èèyàn benue kogi àti cross river ohun èlò benne sísun ẹ̀pà sísun èkùrọ́ ẹran ẹ̀fọ́ ewúro ...
gizdodo gizdodo jẹ́ oúnjẹ̀ tí a fi iwe adìyẹ àti dòdò se ó jẹ́ oúnjẹ àfikún tí a máa ń jẹ ní ilé àti òde ìsọníṣókí àsepọ̀ yìí ni a sè nípa lílo dòdò iwe adìyẹ èròjà ìsebẹ̀ lóríṣiríṣi àlùbọ́sà tàtàṣé àti rodo wọ́n tún máa ń fi káròtù si dòdò àti iwe adìyẹ yẹn ni a máa kọ́kọ́ dín lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ lẹ́yìn náà a máa wá da méjèèj...
adalu àdàlú jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí o gbajúmò láàrín ẹ̀yà yorùbá àwọn igbó náà tún maa ń jẹ ẹ́ gẹ́gẹ́ bí óúnjẹ tàbí ìpanu oúnjẹ náà jẹ́ èyí tí a ṣe láti ara àgbàdo àti ẹ̀wà àdàlú jẹ́ óúnjẹ́ afúnilókún ati oúnjẹ amaradagba jẹ aládùn alailẹgbẹ ìlànà àgbàdo jẹ ọkan nínú àwọn èròjà pàtàkì fun ounjẹ yii àgbà...
nkwobi spicy cow feet jẹ́ oúnjẹ aládùn tó wọ́pọ́ ní àwọn ilé ounjẹ tí a tún mọ̀ sí nkwobi irú oúnjẹ yìí wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹ̀yà igbo ó jẹ́ ọbẹ̀ tí a fi òpó ẹ̀sẹ̀ ẹran màlúù sè àwọn èròjà tí a fi n pèsè rẹ̀ àwọn èròjà tí a ní lò láti fi se ohun ìpanu àwọn ni epo pupa kaun èròjà nọ́tmẹẹ̀gì ewé utazi ata alùbọ́sà àti bẹ́ẹ...
spicy cow feet