raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
doreen awuah ghanaian footballer doreen angelina awuah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 12 óṣu december ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere fum awọn ọdọmọbinrin ghatel gẹgẹbi midfielder |
jane ayiyem ghanaian footballer jane ayiyem jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 19 óṣu october ni ọdun 1997 agbabọọlu naa ṣere fun police fc gẹgẹbi forward |
evelyn badu evelyn badu tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ̀sán ọdún 2003 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède ghana kan tí ó ń ṣeré gẹ́gẹ́ bíi agbábọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù avaldsnes il ti norway àti ẹgbẹ́ obìnrin ghana isẹ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù badu ti gbábọ́ọ̀lù fún hasaacas ladies ní ghana tí ó sì farahàn ní bi ìdíje ìparí ì... |
elizabeth baidu ghanaian footballer elizabeth baidu jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 28 óṣu april ni ọdun 1978 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin bluna gẹgẹbi defender |
adjoa bayor ghanaian footballer adjoa bayor jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹri ti ilẹ ghana ti a bini 17 óṣu may ni ọdun 1979 agbabọọlu naa ṣere fun fc indiana gẹgẹbi midfielder |
mary berko ghanaian footballer mary berko jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu june ni ọdun 1988 agbabọọlu naa ṣere fun police accra gẹgẹbi midfielder |
portia boakye ghanaian international footballer portia boakye jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 17 óṣu april ni ọdun 1989 agbagbọọlu naa ṣere fun djurgårdens if gẹgẹbi defender |
genevive clottey ghanaian footballer genevive clottey jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 25 óṣu april ni ọdun 1969 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder |
gbenga oloukun gbenga oluokun ti a bi ni ọjọ kerinla oṣu kefa odun 1983 jẹ afẹṣẹja lati orilẹ-edenigeria ti o kopa ninu olimpiiki igba ooru 2004 fun orilẹ-ede abinibi rẹ ni iwọ-oorun afirika o ti dojuko awọn afesekubiojo agbaye tẹlẹ ati oludije manuel charr lamon brewster kubrat pulev robert helenius carlos takam vyach... |
olukayode ariwoola acting chief justice of nigeria adájọ́-àgbà olúkáyọ̀dé ariwoọlá cjn gconni wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1958 22 august 1958 jẹ́ adájọ́-àgbà-yányán ti orilẹ̀-èdè nigeria tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn lọ́jọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2022 wọ́n yàn án sípò adájọ́-àgbà-yányán lẹ́yìn tí adájọ́-àgbà t... |
nigerian bar association law organization ẹgbẹ́ nigerian bar association nba jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn adajọ́ tí wọ́n ní ìwé-àṣẹ lọ́rílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ẹgbẹ́ tí wọ́n máa ń jà fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ẹ̀tọ́ ìlànà òfin àti ìjọba tó dára lórílẹ̀-èdè nigeria ọ̀gbẹ́ni olumide akpata ni ààrẹ ẹgbẹ́ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ and the current gene... |
joe el joel amadi tí a mọ̀ sí joe el tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta jẹ́ olórin òǹkọrin àti eléré ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ilé-iṣẹ́ kennis music fọwọ́ síí ní ọdún 2006 ó kópa nínú ìdíje orin-kíkọ tí star quest ní ìlú joslẹ́yìn náà ni ó tún kópa nínú ìdíje ayẹyẹ àjíǹde ọlọ́dọọdún ti i kennis music ẹbí àti ètò-ẹ̀kọ... |
sidi boushaki sidi boushaki 1394-1453 jẹ onimọ-jinlẹ maliki ti a bi nitosi ilu thenia 54 km 34 mi ni ila-oorun ti algiers o dagba ni agbegbe ti ẹmi pupọ pẹlu awọn iwulo islam ti o ga ati awọn ihuwasi laarin itọkasi islam ti àlgéríà ibi ati iran sidi boushaki ez-zaouaoui ni a bi ni 1394 ce ni col des beni aïcha ni abule... |
lateef kayode lateef olalekan kayode ti a bi ni ọjọ keta oṣu keta ọdun 1983 jẹ ojogbon afẹṣẹja ọmọ orilẹede naijiria ti o dije fun akọle cruiserweight wba ni ọdun 2015 ni oṣu kejila ọjọ 3 ọdun 2010 kayode lu omo orilẹ-ede amẹrika edward charles perry lori kaadi boxing showtime kan kayode ṣe afihan isimi ninu ihuwasi di... |
grace anozie <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2022-06-27t174447z</timestamp> <contributor> <username>drhay8</username> </contributor> <comment>o ti ṣẹ̀dá àyọkà nípa ṣíṣe ògbufọ̀ ojú-ewé </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> grace ebere anozie mon ti a bi ni ọjọ kerindinlogun osu keje odun 1977... |
latifat tijani latifat tijani ti a bi ni ọjọ kẹjo oṣu kọkanla ọdun 1981 jẹ elere idaraya agbara gbigbe orilẹ-ede naijiria o gba goolu ninu idije awọn obinrin 45kg ti ere afirika ni odun 2015 ni brazzaville republic of congo ni ọdun 2016 o dije ninu ìdíje àwọn obinrin ni ipele 45kg ni olimpiki àwọn akanda eda ti igba oo... |
bose omolayo bose omolayo ti a bi ni ọjọ kinni oṣu keji odun 1989 je omo orile-ede naijiria o gba ami-eye goolu ni ipele 79 kg ti awọn obinrin ni idije igba ooru 2020 ti o waye ni tokyo japan lẹhinna oṣu die o gba ami-ẹri goolu ninu iṣẹlẹ rẹ ninu idije agbaye ti awon akanda eda ni 2021 ti o waye ni tbilisi georgia ni e... |
ellen coleman ghanaian footballer ellen coleman jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 11 óṣu december ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin strikers gẹgẹbi defender |
elizabeth cudjoe ghanaian footballer elizabeth cudjoe jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 17 óṣu october ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbọrin hasaacas gẹgẹbi forward |
mavis danso mavis danso tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún osù kẹta ọdún 1984 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ọmọ orílẹ̀-ède ghana kan tí ó ń mú ipò olùgbèjà lórí pápá ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède ghana ó wà lára àwọn tí ó kópa ní bi fifa women's world cup ti ọdún 2003 àti fifa ... |
memuna darku memuna darku tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún osù kẹrin ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin ará ilẹ̀ ghana kan tí ó ń ṣeré gẹ́gẹ́ bíi agbedeméjì ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orìlẹ̀-ède ghana ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó kópa ní bi fifa women's world cup ní ... |
mavis dgajmah mavis dgajmah tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejìlá ọdún 1973 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin ọmọ orílẹ̀-ède ghana kan tí ó mú ipò iwájú lórí pápá ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá orílẹ̀-ède ghana ó kópa nínú fifa women's world cup ti ọdún 1999 àti ní fifa world cup women ti ọdún 2003... |
wasila diwura-soale ghanaian footballer wasila diwura-soale jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu september ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin hasaacas gẹgẹbi midfielder |
fafali dumehasi ghanaian footballer fafali dumehasi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ́ ghana ti a bini ọjọ 25 óṣu december ni ọdun 1993agbabọọlu naa ṣere fun accra police gẹgẹbi goalkeeper |
janet egyir ghanaian international footballer janet egyir jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ keje óṣu may ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun afturelding/fram gẹgẹbi defender |
gladys enti ghanaian footballer gladys enti jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ afirica ti a bini ọjọ 21 óṣu april ni ọdun 1975 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper |
linda eshun ghanaian international footballer linda eshun jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kaarun óṣu august ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin hasaacas gẹgẹbi defender |
josephine orji josephine orji ti a bi ni ọjọ kẹjo oṣu kẹrin ọdun 1979 jẹ ojogbon ninu agbara gbigbe ọmọ orilẹ-ede naijiria ni ọjọ kerinla oṣu kẹsan ọdun 2016 o gba goolu ni ẹka + 86kg awọn obinrin ni olimpiki igba ooru àwọn akanda eda ni ọdun 2016 ni orile edè brazil ṣaaju ki o to tẹsiwaju lati ṣeto igbasile agbaye ati... |
shahnez boushaki shahnez boushaki 22 oṣu kẹwa ọdun 1985 algiers jẹ oṣere bọọlu inu agbọn àlgéríà kan ti o ṣere fun mouloudia club ti algiers mca epo idaraya ẹgbẹ gs pétroliers ati ẹgbẹ bọọlu inu agbọn orilẹ-ede awọn obinrin algeria ologba ọmọ boushaki ṣe awọn akoko mẹjọ fun mouloudia club ti algiers lati ọdun 2002 ati ... |
joy onaolapo joy onaolapo ọjọ kerinlelogun osu kejila odun 1982 in sapele nigeria oṣu keje ọdun 2013 je elere-ije àwọn akanda eda lati orile-ede naijiria 2012 o gba ami- eye goolu ni ọdun 52 ẹka agbara gbigbe kg ni ere idaraya ti london ni ọdun 2012 onaolapo ni a fi idi rẹ mulẹ pe o ku ni oṣu keje ọdun 2013 ni eni ọmọ ... |
jacklord jacobs jacklord bolaj jacobs ti a bi ni ọjọ kinni oṣu kinni ọdun 1970 ni ilu benin je omo orile-ede naijiria tele afẹṣẹja ti o dije lati ọdun 1994 si ọdun 2003 gẹgẹbi akeko o ṣe aṣoju orile edè naijiria ni olimpiiki igba ooru ọdun 1992 ni ilu barcelona orilẹ-ede spain ni ọdun kan lẹhinna o gba ami-ẹri fadaka n... |
blessing oladoye blessing oladoye ti a bi ni ọjọ kẹrin oṣu kẹsán odun 2000 je elere ije omo orilẹ-ede naijiria o dije ninu idijẹ isọdọtun mita 4 × 400 ti awọn obinrin ni ere-idije ti ere-idaraya agbaye ni ọdun 2019 ni ọdun 2019 o gba ami-eye goolu ni isọdọtun mita 4 × 400 awọn obinrin ni ere afirika 2019 ti o waye ni r... |
sarah adegoke sarah adegoke ojoibi 1997 je elere tenisi omo orilẹ-ede naijiria lọwọlọwọ oun lo jẹ agbabọọlu tẹnisi ti o ga julọ ni isọri ẹyọkan ti awọn obinrin gẹgẹ bi federation tennis nigeria iṣẹ-ṣiṣe ti o dagba ni ilu ibadan nipinlẹ ọyọ adegoke kọ ẹkọ bọọlu tẹnisi lati owo baba rẹ adedapo adegoke ẹniti o ṣe akiyesi ... |
elizabeth balogun elizabeth balogun ti a bi ni ọjọ kẹsán oṣu kẹsán odun 2000 jẹ agbabọọlu inu agbọn orilẹede naijiria oun gba bọọlu inu agbọn kọlẹji fun ẹgbẹ obinrin kadinali louisville ati ẹgbẹ orilẹ-ede naijiria ile-iwe giga balogun gbe si hamilton heights high school tennessee ni ipele kẹjọ rẹ lati ilu lagos nigeria... |
glory odiase glory odiase ti a bi ni ọjọ karundinlogun oṣu kẹsán odun 1993 jẹ awa kẹkẹ ọmọ orile-ede naijiria o gba ami-eye goolu kan nigba ti o nsoju naijiria ninu idije kẹkẹ gigun akoko idanwo ìdíje obinrin lẹgbẹẹ ayọ okafor rosemary marcus ati gripa tombrapa ni ere gbogbo-afirika ti ọdun 2015 ni congo brazzaville |
victoria macaulay victoria macaulay ti a bi ni ọjọ keje oṣu kejo ọdun 1990 jẹ agbabọọlu inu agbọn ọmọ orilẹede naijiria fun ẹgbẹ agbabọọlu inu agbon orilẹede naijiria ati pe o jẹ aṣoju ọfẹ ti ẹgbẹ bọọlu inu agbọn ti orilẹ-ede awọn obinrin wnba ati ni ọdun 2015 ati 2019 o gba fun chicago sky ni ẹgbẹ bọọlu inu agbọn ti o... |
stefania turkewich stefania turkewich-lukianovych tí a bí ní ọjọ́ karún-úndínlọ́gbọ̀n oṣụ̀ kẹrin ọdún 1898 tí ó sì di olóògbé ní ọjọ́ kejọ oṣù kẹrin ọdún 1977 jẹ́ atorinjọ atẹdùru àti onímọ̀-orin ọmọ orílè-èdè ukraine tí wọ́n dámọ̀ gẹ́gẹ́ bíi obìnrin atorinjọ àkọ́kọ́ ní ukraine àwọn soviet ní ukraine gbẹ́sẹ̀lé iṣẹ́ rè ... |
enejoh abah eneojo joseph abah ti a bi ni ọjọ kerindinlogun osu keji ọdun 1990 je elere badminton omo orilẹ-ede naijiria abah wa lati ipinle kogi ariwa aarin ni orilẹ-ede nigeria o bẹrẹ ṣi ṣere badminton ni ọdun 2003 wọ́n yàn án láti ṣojú orílẹ̀-èdè nàìjíríà nínú ìdíje àgbáyé ní ọdún 2005 ní african junior championship... |
ubong williams ubong williams jẹ agbabọọlu afẹsẹgba kan ti o ṣere bii ohun elo ati eniti oun gba agbedemeji fun abia warriors o gba bọọlu fun delta force tẹlẹ ubong williams edet bẹrẹ iṣẹ bọọlu rẹ lati ọdọ ẹgbẹ ọdọ rẹ karamone fc ti o gba awin akoko losi delta force fc ni nigeria national league ṣaaju ki o to darapọ mọ... |
mary essiful ghanaian footballer mary essiful jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 22 óṣu june ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere fun rivers angels fc gẹgẹbi midfielder |
gloria foriwa ghanaian footballer gloria adwoa foriwa jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 11 óṣu may ni ọdun 1981 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbọrin ghatel gẹgẹbi forward |
nana gyamfuah ghanaian footballer nana amma gyamfuah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kẹrin óṣu august ni ọdun 1978 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbọrin postal gẹgẹbi forward |
priscilla hagan ghanaian footballer priscilla hagan jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kẹrin óṣu april ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere fun konak belediyespor gẹgẹbi forward |
aminatu ibrahim aminatu ibrahim tí a bí ní ọjọ kẹta osù kíní ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède ghana tí òkè-òkun tí ó ń seré gẹ́gẹ́ bí olùgbèjà ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin orílẹ̀-ède ghana ó wà lára àwọn tí ó kópa ní bi fifa women's world cup ti ọdún 2003 àti fifa world cup women ti ọdún 2007 lórí ì... |
juliana kakraba ghanaian footballer juliana kakraba jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 29 óṣu december ni ọdun 1979 |
belinda kanda ghanaian footballer belinda kanda jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini ọjọ kẹta óṣu november ni ọ̀dun 1982 agbabọọlu naa ṣere fun alabama am gẹgẹbi midfielder |
hillia kobblah ghanaian footballer hillia kobblah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini ọjọ keje óṣu july ti ọdun 1991 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder |
alice kusi ghanaian footballer alice kusi jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini ọjọ 12 óṣu january ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun club sebian gẹgẹbi midfielder |
daddy showkey daddy showkey tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ john odafe asiemo tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí daddy showkey jẹ́ gbajúmọ̀ olórin orílè-èdè naijiria irúfẹ́ orin tó ń kọ ni a mọ̀ sí ghetto dance ó gbajúmọ̀ ní ajegunle ní ọdún 1990 sí 1999 orúkọ àbísọ rẹ̀ ni john odafe asiemo àmọ́ orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jé daddy showkey káàk... |
patricia mantey ghanaian footballer patricia mantey jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 27 óṣu september ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun river angels fc gẹgẹbi goalkeeper |
timi dakolo timi dakolo tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kìíní ọdún 1981 jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrin-kalẹ̀ àti agbórin-jáde ó kópa nínú ìdíje idols west africa ní ọdún 2007 ó sì jáde pẹ̀lú ipò kìíní lẹ́yìn aṣeyọrí rẹ̀ yìí ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ sony bmg ó sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn mìíràn |
di'ja hadiza blell tó ti wá ń jẹ hadiza blell-olo tí gbogbo ayé mọ̀ sí di'ja jẹ́ olórin ti orìlẹ̀-èdè naijiria lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú mavin records ní ọdún 2009 ó gbórin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ rock steady tí wọ́n padà yàn gẹ́gẹ́ bíi orin àdákọ urban/rb tó dára jù lọ ní 2009 canadian radio musi... |
eedris abdulkareem eedris turayo abdulkareem ajenifuja tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejìlá ọdún 1974 tí gbogbo ayé mọ̀ sí eedris abdulkareem jẹ́ olórin ilẹ̀ naijiria tó máa ń kọ orin hip-hop rnb àti afrobeat ó tún máa ń kọ orin kalẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ìdíle olórogún ni a bí eedris turayo abdulkareem ajenifuja s... |
eva alordiah elohor eva alordiah tí a bí ní ọjọ́ ketàlá ọdún 1989 tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí eva jé akọrin ti ilè naijiria aṣojú-lóge aránsọ àti olókòwò ó jé ọ̀kan lára àwọn rápà obìnrin tó dára jù lọ ní naijiria |
priscilla mensah ghanaian footballer priscilla mensah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 19 óṣu april ni ọdun 1974 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin portal gẹgẹbi goalkeeper |
vivian mensah ghanaian footballer vivian mensah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 13 óṣu june ni ọdun 1972 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin la gẹgẹbi forward |
fati mohammed fati mohammed tí a bí ní ọjọ́ kẹrin osù kẹfà ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá obìnrin ará ilẹ̀ ghana kan tí ó ń ṣeré gẹ́gẹ́ bí asọ́lé ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá obìnrin ti orílẹ̀-ède ghana ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó kópa ní bi 2003 fifa women's world cup àti 2007 fifa world cup ... |
m'bala nzola m'bala nzola ti a bi ni ọjọ kejidinlogun oṣu kẹjọ ọdun 1996 jẹ alamọdaju agbabọọlu ti orilẹ-ede angola ti o ṣere bi agbabọọlu fun olugba serie a spezia ati ẹgbẹ orilẹ-ede angola ise egbe agbabọọlu ni 28 oṣu kini 2015 nzola gba bọọlu akọbgba ti ọjọgbọn rẹ pẹlu académica de coimbra ni 2014-15 taça da liga ni... |
alima moro ghanaian footballer born 1983 alima moro jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ karun óṣu february ni ọdun 1983 agbabọọlu naa ṣere fun tavagnacco gẹgẹbi goalkeeper |
dice ailes shasha damilola alesh tí orúkọ ìnagije rẹ̀ ń jẹ́ dice ailes jé akọrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrinkalẹ̀ àti rápà ní oṣù keje ọdún 2014 ó tẹwọ́ bòwé pẹ̀lú chocolate city wọ́n yàn án fún rookie of the year ní the headies 2016 ní ọdún 2016 orin rẹ̀ tooxclusive ṣe àfihàn orin rè tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ miracle ó sì... |
mercy myles ghanaian footballer mercy myles jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti o ṣere gẹgẹbi midfielder nibi ti elere naa ti kopa ninu ere gbogbo ilẹ afirica ti ọdun 2011 |
lily niber-lawrence ghanaian footballer lily niber-lawrence jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini ọjọ 23 óṣu june ni ọdun 1997 agbabọọlu naa ṣere fun primera nacional gẹgẹbi midfielder |
nina norshie ghanaian association football player nina norshie jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 14 óṣu september ni ọdun 2001 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin berry gẹgẹ̀bi defender |
patricia ofori ghanaian footballer patricia ofori jẹ agbabọọ̀lu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kẹsan óṣu june ni ọdun 1981 ti o si ku ni ọjọ 20 óṣu april ni ọdun 2011 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender |
sheila okai sheila okai tí a bí ní ọjọ kẹrìnlá osù kejì ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ará ilẹ̀ ghana kan tí ó ń ṣeré ní ipò agbedeméjì àti iwájú ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède ghana ó wà lára àwọn tí o kópa ní bi fifa women's world cup ti ọdún 1999 àti ní fifa wo... |
florence okoe ghanaian footballer florence okoe jẹ agbabọọlu lobinrin ti ilẹ ghana ti a bini ọjọ 12 óṣu november ni ọdun 1984 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin ghatel gẹgẹbi midfielder |
priscilla okyere ghanaian footballer priscilla okyere jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kẹfa óṣu june ni ọdun 1995 |
sonia opoku ghanaian footballer sonia opoku jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti o ṣere fun club turkey gẹgẹbi midfielder |
vida opoku ghanaian footballer vida opoku jẹ agabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 15 óṣu december ni ọdun 1997 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin olympique marseille gẹ̀gẹbi defender |
myralyn osei agyemang ghanaian footballer myralyn “mimi” nartey jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ karun óṣu november ni ọdun 1981 agbabọọlu naa ṣere fun portland rain gẹgẹbi forward |
sandra owusu-ansah ghanaian association football player sandra owusu-ansah jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini ọjọ 29 óṣu january ni ọdun 2000 agbabọọlu naa ṣere fun zfk spartak subotical gẹgẹbi forward |
blackface ahmedu augustine obiabo tí a bí ní ogwule ìlú agatu ipinle benue naijiria tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ blackface naija tàbí blackface jẹ́ olórin oníjó àti akọrin-sílẹ̀ ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kọrin african queen pẹ̀lú 2face idibia ní ọdú 2004 |
ahmad hasan amrohi indian muslim scholar ọ̀gbẹ́niahmad hasan amrohi eni tí a tún mọ̀ sí muhaddith amrohi tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta 1850 ọdún 1912 jẹ́ jẹ́ ọ̀mọ̀wé làmìlaka mùsùlùmí ọmọ indian tí ó jẹ́ ọ̀gá àkọ́kọ́was madrasa shahi ní moradabad ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́-àná ti darul uloom deoband tí ó sìn tún jẹ́ ọ̀k... |
madrasa shahi islamic seminary in india ọ̀gbẹ́ni madrassa shahi tí a tún mọ̀ sí jamia qasmia jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mùsùlùmí ní moradabad uttar pradesh àwọn at àpáta-dìde ọmọ mùsùlùmí ni wọ́n dá a sílẹ̀ lọ́dún 1879 lábẹ́ ìṣàkóso onímọ̀-àgbà ẹ̀kọ́ mùsùlùmí muhammad qasim nanautawi ẹni tí ó tún dá darul uloom deoba... |
moradabad ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the town in uttar pradesh india fún its namesake district ẹ wo moradabad district fún other uses ẹ wo moradabad disambiguation moradabad jẹ́ ìlú-ńlá àti olú-ìlú ní moradabad district ní ìpínlẹ̀ uttar pradesh ní indian moradabad jẹ́ ìlú tí ó tẹ̀dó sẹ́bàá òdò ramganga tí kò jìnnà sí olú-ì... |
brymo ọlawale ọlọfọrọ tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ olawale ibrahim ashimi tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún ọdún 1986 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ brymo jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè naijiria akọrin oṣèré orí-ìtàge àti òǹkọ̀wé ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú chocolate city ní ọdún 2010 àmọ́ wọ́n fi ẹ̀sún kàn án pé ó tàpa sí òfin ìwé-iṣẹ... |
masihuzzaman khan masīhuzzamān khān 1840 17 december 1910 fìgbà kan jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè india tó jẹ́ gíwá kejì fún ilé-ìwé darul uloom nadwatul ulama òun ni olùkọ́ fún mir laiq ali khan àti mahboob ali khan ìtàn ayè masihuzzaman khan a bí masīhuzzamān khān ní ọdún 1840 1256 ọdun hijri ah ní ìlú shahjahanp... |
abul kalam qasmi indian scholar critic and poet 19502021 ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ abul kalam qasmi shamsi abul kalam qasmi 20 december 1950 8 july 2021 fìgbà kan jẹ́ onímọ̀ orílẹ̀-èdè india alárìísí àti akéwì ní èdè urdu tó fígbà kan jẹ́ díìnì faculty of arts ní aligarh muslim university òun ni olóòtú ìwé tehzeeb-ul-akh... |
mazhar nanautawi muḥammad mazhar nanautawi 18211885 fìgbà kan jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè india àti àjà fétò òmìnira tó kópa pàtàkì nínú ìdàgbàsókè mazahir uloom ó kópa nínú battle of shamli ìtàn ìgbésíayé mazhar nanautawi a bí muḥammad mazhar sínú ìdílé siddiqi family of nanauta ní ọdún 1821 bàbá rẹ̀ lutf ali tá... |
noor alam khalil amini noor alam khalil amini tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá ọdún 1952 tí ó sìn ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2021 onímọ̀ àgbà mùsùlùmí ọ̀mọ̀wẹ́ àti oǹkọ̀wé èdè arabic àti urdu ọmọ indian ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àgbà èdè lárúbáwá àti lítíréṣọ̀ ní darul uloom deoband ìwénrẹ̀ falastin fi intezari ... |
mamluk ali nanautawi mamluk ali nanutawi èyí tí wọn tún máa ń pè ní mamluk al-ali nanautawi tí wọ́n bí lójó keje oṣù kẹwàá ọdún 1789 tí ó ṣaláìsí lọ́dún 1851 jẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ mùsùlùmí súńní tí orílé èdè índíà tí ó ṣíṣe-sìn gégé bí adarí fún èdè lárùbáwá ní zakir husain delhi college lára àwọn akékòó rẹ̀ ní muhammad was... |
hafizur rahman wasif dehlavi indian muslim scholar hafizur rahman wasif dehlavi ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1910 ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹ̀ta ọdún 1987 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè índíà ọ̀jọ̀gbọ́n lórí ìmọ̀ mùsùlùmí agbẹjọ́rò lámèyítọ́ iṣẹ́-ọnà lítíréṣọ̀ àti akéwì èdè urdu ó sì tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdarí ilé kéwú kan tí ó ń jẹ́ madrasa ... |
abu salman shahjahanpuri abu salmān shahjahānpūri tí orúkọ àbísọ ń jẹ́ tasadduq hussain khan ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kiní ọdún 1940 ní shahjahanpur ìgbésíayé àti iṣẹ́ rẹ̀ abu salmān shahjahānpūri tí orúkọ àbísọ ń jẹ́ tasadduq hussain khan ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kiní ọdún 1940 ní shahjahanpur ó lọ sí í ilé ìwé ní madrasa saeedia... |
florence banku obi florence banku obi jẹ́ òṣìṣẹ́ akadá ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà òǹkọ̀wé àti ọ̀jọ̀gbọ́n ti ìmọ̀ ẹ̀kọ́ tí ó yàtọ̀ ó jẹ́ gíwá kọkànlá ti fásitì calabar àti gíwá-obìnrin àkọ́kọ́ láti ìgbà tí wọ́n tí dá ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà lẹ́yìn tí wọ́n ti yàn án gẹ́gẹ́ bí adarí tuntun ní sẹ́nítọ̀ ovie omo-agege tí ó jẹ́ alága... |
wasif dehlawi hafizur rahman wasif dehlavi 10 february 1910 13 march 1987 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè india alárìíwísí àwọn ìwé lítíreṣọ̀ lóríṣiríṣi àti akéwì èdè urdu tó jẹ́ olórí madrasa aminia láti ọdún 1955 wọ 1979 ó kópa nínú ètò ìgbòmìnira ti ìlú india ó sì kọ oríṣìíríṣìí ìwé bíi adabī bhūl bhulayyān̲ urdū ... |
adésọjí adérẹ̀mí |
jumiat ulama-e-hind council of indian muslim theologians ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ jamaat-e-islami hind jamiat ulema-e-hindd tàbí jamiat ulama-i-hind jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ẹgbẹ́ adarí ọ̀mọ̀wé mùsùlùmí tí ó jẹ́ ti deobandi ilé-ìwé amòye ti ìpìlẹ̀ rẹ̀ wáyé ní oṣù kọkànlá ọdún 1919 láti ọwọ́ ẹgbẹ́ ọ̀mọ̀wé mùsùlùmí pẹ̀lú abdul... |
muhammad ali mungeri muḥammad ali mungeri tí a bí ni ojó kejidinlogun oṣù kẹfà ọdún 1846 rí ọ sí jáde láyé ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn ọdún 1927 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tí ó dá nadwatul ulama àti ẹni àkọ́kọ́ tí ó ṣe olùdarí darul uloom ó sí jẹ́ onímọ̀ islamic seminary ní lucknow ó kọ àwọn ohùn tí ó lòdì sí ẹsìn kìtẹ̀ẹ̀níì àti ẹsìn... |
ijteba nadwi muḥammad ijteba nadwi 29 september 1933 20 june 2008 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè india tí ó sì tún fìgbà kan jẹ́ olórí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ èdè lárúbáwá ní ilè iwè giga ti jamia millia islamia kashmir àti ilè iwè giga allahabad nadwi kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní darul uloom nadwatul ulama damascus university àti aligarh ... |
taha karaan taha karaan 2 june 1969 11 june 2021 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè south africa àti amòfin òun ni olórí muslim judicial council ti ilẹ̀ south africa nígbà náà òun ni olùdásílè mahajjah research institute àti dar al-uloom al-arabiyyah al-islamiyyah ní strand western cape ìtàn ìgbésíayé rẹ̀ ọjọ́ kejì oṣù ... |
kafilur rahman nishat usmani kafīlur rahmān nishāt usmānī 5 march 1942 1 august 2006 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè india amòfin àti akéwì tó jẹ́ mufti ti darul uloom deoband òun ni ọmọ-ọmọ azizur rahman usmani ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní darul uloom deoband àti aligarh muslim university ó ṣe ògbufọ̀ fatawa 'alamgiri sí èdè... |
rafiq ahmad pampori rafiq ahmad pampori born 13 february 1956 jẹ́ onímọ̀ mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè india onímọ̀ àti òǹkọ̀wé tó ṣe ìdásílẹ̀ darul uloom ilahiya tó jẹ́ ilé-ìwé islam ní ìlú srinagar ahmad kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní sri pratap college àti government medical college srinagar òun ni rector darul uloom ilahiya ní srinaga... |
nizamuddin asir adrawi indian historian 19262021 nizāmuddīn asīr adrawi tí a sì mọ̀ sí asīr adrawi láti ọdún 1926 títí dé ọjọ́ ogún oṣù karùn-ún ọdún 2021 jẹ́ onímọ̀ ìjìnlè mùsùlùmí ti ilẹ̀ india ò sí tún jẹ́ òǹkọ̀wé ìtàn nípa ìgbésí ayé ẹni àti òǹkọ̀wé nínú èdè urdu ó ṣe ìdásílẹ̀ madrassa darus salam ni ìlú adari ó sì... |
nike art gallery nike art gallery jẹ́ orúkọ ibi ìṣàfihàn àwòrán kan ní ìlú èkó àti ní ìlú ọ̀ṣun tí arábìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ nike davies-okundaye dá sílẹ̀ ilé ìṣàfihàn àwòrán yìí jẹ́ lára èyí tí ó tóbi jù lọ ní orílẹ̀-èdè west africa iyàrá tó wà ní ilé-alájà gíga márùn-ún tí ó sì fí àwọn àwòrán tó ń lọ bíi ẹgbàà... |
charly boy ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the nigerian singer fún the american rapper ẹ wo chalie boy charly boy tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ charles chukwuemeka oputa ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹ̀fà ọdún 1950 ó tún ń jẹ́ cb his royal punkness àti area fadaakọrin àti olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà olùkọ́ni lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán atèwé-ì... |
yemi adamolekun nigerian executive director yemi adamolekun jẹ́ aláṣẹ olùdarí enough is enough ó má ń ṣe ìwọ́de ìjọba tó dára ní nàìjíríà ó tún jé àgbà aláàbáṣepọ̀ center for strategic and international studies àwọn ìtọ́kasí |
roseline osipitan olorì roseline omolará òṣípìtàn jẹ́ aláàkóso ìṣòwò nàìjíríà àti ọmọ ọba ilẹ̀ yorùbá ó jẹ́ ààrẹ àti alága ẹgbẹ́ olómìnira ti petroleum marketers association of nigeria's women association ó sì tún jẹ́ olùdásílẹ̀ ti first royal oil and gas òun ló mú oyè ti yèyé ọba ti ìlú ìtori dání ìgbésí ayé wọ́n bí o... |
bukola oriola nigerian activist and journalist nigerian activist and journalistbukola oriola tí a bí nínu odùn 1976ó jè oníròyìn omo naìjíríà ní ìlú america oún gbé ní anoka county minnesotao bi omo okunrin ti oruko re je samuel jacob lasiko to wa ni america o lo odun mefa lori ise oniroyin ni odun 2005o wa si ilu oyin... |
olúfúnkẹ́ bàrúwá olúfúnkẹ́ bàrúwájẹ́ aṣègbèfábo àti sọ̀rọ̀sọ̀sọ̀ àwùjọ pàápàá jù lọ lórí ìjọba àti ètò-ìṣèjọba ọmọ orílẹ̀-èdè nigeria fún nǹkan bí ogún ọdún ó ti jẹ́ gbajúmọ̀ àti ọkàn gbòógì nínú àwọn aṣáájú lámèyító lórí ètò-àyíká àti àtúnṣe lórílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìjọba àwọn àjọ abẹ́lé àti àjọ òkè-òku... |
mo'cheddah modupe-oreoluwa oyeyemi ola ti abi ni ojo kerindinlogun osu kewaa odun 1990 ti oruko ori itage re si n je mo'cheddah nigba miran ti a le pe ni mocheeda tabi mocheddah ti o je okorin ati rapper ti orile ede naijiria o se ifilole studio debut album re ti o pe ni franchise celebrity ni odun 2010 nigba ti o wa p... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.