raw_text
stringlengths
2
128k
abuja fct
abaji
nigerian lgas
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ akinyele akinyele jé agbègbè ìjoba ìbílè ní ìpínlè oyoorílè èdè nàíjíríà ó jé okan lára àwon ìjoba ìbílè mokànlá tí ó parapò di ìlú ìbàdàn ó wà ní agbègbè móníyà wón dá a sílè ní odún 1976 ó pa ààlà pèlú ìjoba ìbílè afijio ní apá àríwáìjoba ìbílè lagelu si apa ilà oòrùn wón fi so orúko olóògbé olúb...
móníyá moniya je ilu ni ipinle oyo ati oluilu agbegbe ijoba ibile akinyele
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ afijió agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ afijio jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọb a ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní nàìjíríà olú-ìlú rè wà ní jobele ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 722 km2 àti iye ènìyàn tó tó 134173 ní ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006 kóòdù ìfìwéránṣẹ́ ìlú náà ni 211 ìtàn ní ọdún 1989 ìjọba àpapọ̀ ológun ìgbà náà...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ egbeda egbeda jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú egbeda wọ́n gé agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ egbeda kúrò nínú agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ lagelu ní ọdún 1989 kóòdù ìfíwéránṣẹ́ ìlú náà ni 200109 ìwọ̀n ilẹ̀ ìlú yìí ní ilẹ̀ tó tóbi tó 191 km2 ài iye...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá ìbàdàn ibadan north ni ijoba ibile ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni orilede nàìjíríà ilu ilese igakan duro ni agodi ibadan postal code fun adugbo yen ni 200 ìwọ̀n ilẹ̀ o ni agbegbe 27 km2 ati iye 856988 gege bi ijoba ipinle oyo ti so ni odun 2017 o de tun ni akeko to daa ati ise eto oro aje pelu yunifasiti a...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìlàòrùn ìbàdàn ibadan north-east yoruba ariwa-ilaorun ibadan jẹ́ àgbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ni ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjíríà olú ilẹ̀-iṣẹ́ wọn wá ní ìwó road àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà ìránṣẹ́ sí tí agbègbè náà ni 200 ìwọ̀n ilẹ̀ ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tí 18 km2 àti iye àwọn ènìyàn tó jẹ́ 330399 ni ètò ìkànìyàn 2006
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìwọòrùn ìbàdàn ibadan north-west jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlè ọ̀yọ́ nàìjíríà olú ilé ìṣe wá ní dugbe/onireke àmì ìfi lẹ́tà ranṣẹ agbègbè sí ni 200 demographics óní agbègbè 26 km2 àti iye àwọn ènìyàn tó jẹ́ 152834 ní ètò ìkànìyàn 2006
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ olórunsògo agbegbe ijoba ibile olorunsogo je ibile ijoba ni ipinle oyo naijiria oluilu re ni igbeti
ìgbẹ́tì <ns>0</ns> <revision> <parentid>545517</parentid> <timestamp>2021-07-14t104943z</timestamp> <contributor> <username>olaniyan olushola</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> igbeti je ilu ni ipinle oyo ati ibujoko agbegbe ijoba ibile olorunsogo
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù-ìwọòrùn ìbàdàn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù-ìwọ̀òrùn ìbàdàn jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ wà ní oluyole estate ní ìbàdàn àwọn agbègbè tó wà ní ìlú náà ni ring-road oke-ado oke-bola gege born-photo àti isale-osi ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 40 k...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gbọ̀ngàn ibarapa agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gbọ̀ngàn ibarapa jẹ́ ọ̀kan lára àọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní nàìjíríà agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gbọ̀ngàn ibarapa jẹ́ àpapọ̀ ìlú igbo-ora àti idere olú-ìlú náà wà ní igbo-ora ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 440 km2 àti iye ènìyàn tó tó 102979 ní ìka orí tó wáyé...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ibarapa agbegbe ijoba ibile ilaorun ibarapa jẹ́ ọ̀kan lára àọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní nàìjíríà àwọn ènìyàn ìbàràpá ló pọ̀ jù níbẹ̀ olú-ìlú náà wà ní eruwa ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 838 km2 àti iye ènìyàn tó tó 118226 ní ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006 kóòdù ìfìwérá́nṣẹ́ ìlú náà n...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ido agbegbe ijoba ibile ido je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo ido ni oluilu re
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìséyìn iseyin jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjíríà ó jẹ̀ dede ariwa ilẹ ibadan ìlú náà ní onka ènìyàn tí o to 236000 gẹ́gẹ́ bí àjọ agbaye ti fi múlẹ ní ọdún 2005 eleyii tí o padà le ti ọ sí di 362990 ni ọdún 2011 ti ọ sí ni àlà ilé tí o jẹ
mose
gregorian calendar
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìrẹ́pọ̀ ìrépò jé agbègbè ìjoba ìbílè ní ìpínlè òyó ní orílè èdè nàìjíríà àwon olú ìlú rè wa ni ìlú kìsíò nì agbègbè tí ó tó 984km² àti iye ènìyàn tí ó tó 122553 níye níbí ònkà ènìyàn tí odún 2006 km2 orúko oba ìlú kìsí ni ìjoba ìbílè agbègbè ìrépò ni iba ti ìlú kìsí orúko iba ti ìlú kìsí ni oba mos...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kajola agbegbejẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ni ìlú ọ̀yọ́ ilẹ̀ nàìjíríàngbọ̀ngàn olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ yìí wà ní agbègbè òkehò
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ lagelu lagelu jẹ́ àgbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ni ìpínlè ọ̀yọ́ nàìjíríà olúùlú rẹ̀ wá ni ìlú tí ìyànà ọffà ó jẹ́ àgbègbè 338 km2km2 àti and iye ènìyàn147957 ní òǹkà ti ọdún 2006 a ṣe àtúnpín àgbègbè ìjọba ìpínlẹ̀ lágelú sì ọ̀wọ́ mẹ́rìnlá tí ń se ajara/opeodu apatere/kuffi/ogunbode/ogo arulogun ehin/kelebe ...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá ogbomosho agbegbe ijoba ibile ariwa ogbomosho jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjíríà tí olú ile ìṣẹ́ rẹ̀ wà ní òpópónà ìlọrin tí alága wọn lọ́wọ́lọ́wọ́ sí jẹ́ ọ̀gbẹ́ni kabir àkànjí ìjọba ìbílẹ̀ yí jé ibi tí a gbé ọkàn lára ilé ìwé ẹ̀kọ́ gíga ladoke akintola university of techno...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù ogbomosho ogbomosho south jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní orílẹ́-èdè nàìjíríà olú ìlú gúúsù ògbómọ̀ṣọ́ wà ní agbègbè arówómọlé ní ìlú ògbómọ̀ṣọ́ ó fẹ̀ ní ìwọ̀n 88km² ní ọdún 2006 wọ́n ka iye ènìyàn tí ó wà níbè sí 185815 nọ́mbà ìfi lẹ́tà jíṣẹ́ sí ìlú náà ni 210 ìjọba ológun dá ag...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ọ̀yọ́ agbegbe ijoba ibile ilaorun oyo je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo kosobo ni oluilu re awon abule
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìwọòrùn ọ̀yọ́ agbegbe ijoba ibile ilaorun oyo je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo ojongbodu ni oluilu re awon abule
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ atiba atiba jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjíríà olúùlú rẹ̀ wà ní ìlú ọffà mẹ́ta ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tí ó jẹ́ 1757 km2 àti iye àwọn ènìyàn tí ó jẹ́ 168246 ní ètò ìkànìyàn 2006 àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà ìránṣẹ́ àgbègbè náà ni 203 àwọn àgbègbè kọ̀ọ̀kan lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ àtìbà nìwọ̀nyìí agúnpopo aremo ash...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ atigbo agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ atigbo jẹ́ agvègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tí ó fìdí kalẹ̀ sí tedé nọ́mbà ìforúkọ sílẹ̀ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú tde amioro ifiletaranse 203
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìwọòrùn ṣakí ìjọba-ìbílẹ̀ ìwọòòrùn ṣakí jẹ́ àgbègbè ìjọba-ìbílẹ̀ ni ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ṣakí ní ibùjókòó rẹ̀ ìlú ṣakí wà ní ìpẹ̀kun ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ibẹ̀ ni ibùdó center of ẹkùn ìdigun kejì àwọn ọmọoogun orílẹ̀ èdè nàìjíríà ilé ẹ̀kọ́ gbogboǹṣetops ilé ẹ̀kọ́ ìkọ́ni-mọ̀ọ́ṣe ìlé èkó ológ...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ṣakí agbegbe ijoba ilaoorun saki je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo ago-amodu ni ibujoko re awon abule nomba iforukosile moto bere pelu shk amioro ifiletaranse 203
governor of oyo state
states of nigeria
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìtẹ̀síwájú itesiwaju jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òtu ni ibùjókòó rẹ̀ wà ó ní agbègbè ti 1514 km2 àti òǹkà ènìyàn ti 128652 gẹ́gẹ́ bíi ètò ìkànìyàn ọdún 2006 àmìọ̀rọ̀ ìfilẹ́tàráńsẹ́ agbègbè náà ni 202
ààlà ìtóbi tabi ìfẹ̀ je piposi to n so bi odeoju elegbeegbe-meji kan se tobi si awon eyo awon eyo fun wiwon ifesi are a = 100 square metres m² hectare ha = 100 ares a = 10000 square metres square kilometre km² = 100 hectares ha = 10000 ares = 1000000 square metres square megametre mm² = 1012 square metres square foot =...
area
ìlọ́poméjì máìlì ìlọ́poméjì máìlì mi² je eyo iwon ifesi
square mile
1 e11 m² to help compare orders of magnitude of different geographical regions we list here surface areas between 100000 km2 and 1000000 km2 see also areas of other orders of magnitude
àkójọ àwọn àmìọ̀rọ̀ ìpè tẹlifónù orílẹ̀-èdè amioro ipe telefonu fun awon orile-ede
akojo awon amioro ipe telifonu orile-ede
list of country calling codes
nọ́mbà tẹlifónù ní nàìjíríà oniru ipe lati pe ni naijiria oniru yi n je lilo xxx xxxx awon ipe ninu amioro agbegbe kan 01 xxx xxxx awon ipe lode eko +234 1 xxx xxxx awon ipe lode nigeria 009 international direct dialing code
+234
telephone numbers in nigeria
àmìọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè fún top-level domain
country code top-level domain
wat
agbègbè àkókò àkókò-agbègbè jẹ́ àwọn àgbègbè ayé tí àkókò wọn papọ̀ tàbí jẹ́ ìkan náà
earth
time zone
owóníná owóníná le je ohun ti won fi n se kara-kata ni awujo ilu ipinle tabi orile-ede kan fun apere naira nàìjíríà tabi owo wewe ati owo odidi owo ohun ti won je apa didimu ipese owo orile-ede kan apa keji ipese owo je awon ti won je fifipamo si ile-ifowopamo
currency
ìlọ́poméjì mítà ìlọ́poméjì mítà ilopomeji metre ni eyo dida si fun ifesi ti ami-idamo rre je m2 33a1 ninu unicode o je titumo gege bi ifesi anigunmerin ti awon egbeegbe re ni iwon mita kan pere
square metre
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ iwajowa agbègbè ìjoba ìbílè ìwàjowá` jé agbègbè ìjoba ìbílè ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tí ibùjókò rè wà ní ìwéré-ilé ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìlú ìwéré jẹ́ ìlú tó lààmì-laaka tí ó wà lábẹ́ àkóso ìlú ọyọ́ ní ilẹ̀ yorùbá láti ayé atijọ́ nípa akínkanjú àti ogun jíjà pẹ̀lú bí ìlú ọ̀yọ́ ṣe jẹ́ ibùjókòó agbára láyé ...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá ibarapa agbegbe ijoba ibile ariwa ibarapa je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo ayete ni ibujoko re wa awon abule nomba iforukosile moto bere pelu ayt amioro ifiletaranse 201
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ olúyọ̀lé agbegbe ijoba ibile oluyole je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo idi-ayunre ni ibujoko re wa awon abule nomba iforukosile moto bere pelu yre amioro ifiletaranse 200
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ogo-oluwa agbegbe ijoba ibile ogo oluwa je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo ajaawa ni ibujoko re wa awon abule nomba iforukosile moto bere pelu ajw amioro ifiletaranse 210
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ surulere ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ agbegbe ijoba ibile surulere je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo surulere ni oluilu re awon abule
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ona ara ọ̀nà àrà jé ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ orílé-èdè nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú àkánrán ó ní agbègbè kìlómítà 290 pẹ̀lú òǹkà ènìyàn 265059 ní ètò ìkànìyàn ọdún àmìọ̀rọ̀ ìfilẹ́tàráńṣẹ́ agbègbè náà ní igba
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ orelope agbegbe ijoba ibile orelope je agbegbe ijoba ibile ni ipinle oyo igboho ni oluilu re awon abule
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ori-ire agbègbè ìjọba ibilẹ jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú ìkòyí ó ní agbègbè 2116km² àti iye ènìyàn tí ó tó 150628 ní ètò ìkà ènìyàn tí ó wà yé ni ọdún 2006 àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà rán ṣẹ́ agbègbè ní 210 ó ní ìwọ̀n-ilẹ̀ tó tó 2116 2 ojú ọjọ́ iwòn ìgbóná tí ìkòy...
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù-ìlàòrùn ìbàdàn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù-ìlàòrùn ìbàdàn jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ wà ní gbọ̀ngán mapo kóòdù ìfìwéránṣẹ́ ìlú náà ni 200 ìwọ̀n ilẹ̀ ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 17 km2 àti iye ènìyàn tó tó 266046 ní ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006
nnewi nnewi je ilu ni ipinle anambra naijiria
pisac pisak je abule ni orile-ede peru
lima lima ni oluilu ati ilu titobijulo ni peru
quito kito kitu ni oluilu ecuador
guayaquil guayaquil tabi santiago de guayaquil ni ilu titobijulo ni ecuador ibe na si ni ebuta nla wa
caracas karakas ni oluilu fenesuela
awon ijoba ibile naijiria
àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ kàtsínà <onlyinclude>akojo awon alamojuto ati awon gomina ipinle katsina ipinle katsina je didajo ni 1987 nigbati o je yiyo kuro ninu ipinle kaduna </onlyinclude>
joe biden joseph robinette biden jrtí a bí ní november 20 1942 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè amerika àti ààrẹ amẹ́ríkà lọ́wọ́ lọ́wọ́ ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú democratic party óun ni ìgbàkejì ààrẹ orílè-èdè amerika láàrin ọdún 2009 sí 2017 lábé isejoba ààrẹ barack obama òun sì ni senato tí ó ṣe asoju delaware láàrin ọdún 1973 ...
roman catholic
ìpínlè hawaii
àtòjọ àwọn ààrẹ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ààrẹ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ní olórí ìṣèjọba àti àti olórí orílẹ̀ èdè náà tí wọ́n dìbò yàn láti darí wọn fún ọdún mẹ́rin gbáko láti ọdún 1789 tí wọ́n ti ṣẹ̀dá àyè ìṣèjọba yìí ènìyàn mẹ́rìnlélógójì 44 ló ti jẹ ààrẹ lórílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ààrẹ-àná george washington ni ààrẹ àkọ́kọ́ tí ó jé l...
list of presidents of the united states
ààrẹ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà
ààrẹ ilẹ̀ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà aare ile orile-ede amerika ni olori orile-ede ati olori ijoba orile-ede amerika aare lo unsolori apa apase ijoba apapo ati oga patapata ile-ise ologun ile amerika
bill clinton william jefferson bill clinton bibi william jefferson blythe iii august 19 1946 je aare orile-ede amerika 42ji lati 1993 to 2001
george h w bush george herbert walker bush june 12 1924 november 30 2018 je aare orile-ede amerika 41ni lati 1989 de 1993 otun je igbakeji aare si ronald reagan lati 1981 de 1989 ati baba george w bush
íṣẹ́ológun íṣẹ́ológun ni agbajo ti o ni ase lati lo ipa nigba miran pipo pelu ohun ijagun lati da abo bo orile-ede won lati koju ewu gidi tabi to le wa ologun ni a n pe gbogbo ohun to je mo ti ise-ologun awon ise-ologun nigba miran n sise bi awujo ninu awujo nipa nini awujo ologun ti won nikan isuna eko iwosan ati awon...
military
mihai ghimpu
vlad filat
albert 2k ilẹ̀ mónakò
jean-paul proust jean-paul proust 3 march 1940 8 april 2010 jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ìlú faransé àti manegasque o ṣiṣẹ́ sin ìlú monaco gẹ́gẹ́ bí mínísítà ìpínlẹ̀ ti monaco tẹ́lẹ̀ rí ìgbésí ayée rẹ̀ wọ́n bí jean-paul proust ní 3rd of march 1940 ní vaas srthe ní faranse ó kẹ́ẹ̀kọ́ gboyè ní école nationale d'administration isẹ́ ó...
tsakhiagiin elbegdorj tsakhiagiin tsakhia elbegdorj mongolianцахиагийн элбэгдорж
sükhbaataryn batbold
filip vujanović
milo đukanović milo đukanović montenegrin cyrillic мило ђукановић pronunciation 'milɔ 'dʑukanɔʋitɕ ojobi 15 february 1962 ni alakoso agba orile-ede montenegro lowolowo igba kefa re niyi lori aga
muhammad vi of morocco
armando guebuza armando emílio guebuza ojoibi 20 january 1943 ni murrupula igberiko nampula je oloselu ati aare orile-ede mozambique lati 2005
marcus stephen
ram baran yadav ram baran yadav ojoibi 4 february 1948 ni aare ile nepal lowolowo
madhav kumar nepal madhav kumar nepal माधवकुमार नेपाल ibi march 6 1953 ni alakoso agba ile nepal o de ori aga ni may 25 2009
beatrix ilẹ̀ nẹ́dálándì
jan peter balkenende jan peter balkenende ojoibi may 7 1956 je oloselu ara hollandi omo egbe oloselu christian democratic appeal be sini lati july 22 2002 ohun ni alakoso agba ile hollandi
anand satyanand sir anand satyanand gnzm qso kstj ojoibi 22 july 1944 ni gomina agba 19k lowolowo orile-ede new zealand teletele o sise bi agbejoro adajo ati alaja
john key john phillip key ojoibi 9 august 1961 ni alakoso agba 38k lowolowo orile-ede new zealand ati olori new zealand national party
daniel ortega josé daniel ortega saavedra nikarágúà ni oṣu kọkanla ọdun 2021 ti tun dibo fun ọdun kẹrin ọdun marun pẹlu 75 ti ibo ni ibamu si awọn abajade osise apakan akọkọ ti o tu silẹ nipasẹ igbimọ idibo giga julọ