text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Dara Owuro! 😂 Mo gbede dada..... #nigeria #africa #yoruba #idontknowwhatimsaying #mytranslatorismadnow @user ok so good morning all 🌞
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òye olórí ìbàdàn ni a mọ̀ sí baálé ìbàdàn ṣùgbọ́n àyípadà dé sí orúkọ oyè yìí ní ọdún sí olúbàdàn ní àsìkò ọba okùnọlá abass alẹ́ṣilóyè
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#OroAmoye Omode yoo dagba, Agba ko ni di Olorun, ipokipo to wu ki eda wa laye, ki eda se jeje tori aye o lo bi opa ibon
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, O ma se o ! Wasilatu omo Wasiu Ayinde ku lojiji: Asiko yii ko dara rara… https://t.co/0VfD9MhMGx
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user Alagba Abati eku akitiyan, Ki eledua ki o ko gbo gbo wa mo se, ekabo si ori oro ip ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tok say iku enu atiku loma npa still omugo agba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: .@user ema binu o, lori oro #NigeriaDecides2019 eba wa so fun Alaga eto idibo Omowe Yakubu pe wan ponu. Oku di…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣe ìtànká ìfẹ́ ní gbogbo ibi tí o bá ń lọ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni fìgbà kan wá sọ́dọ̀ rẹ láìdunnú kúrò mother theresa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹdan kì í kú, kì í rùn. Ojú Ẹdan kì í fọ́ nílédì. #Yoruba #Ogboni #Ogboran https://t.co/66pPsXkMrG
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àsìkòo ṣàngó ní ìlù gángan gànkú ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ dùndún àti ijó látíkípa lauku àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ dé ìlù kàtúngà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user e senu pupo Ao ma riyin ba o Ima yin o nigbemi """" a ì í dúpẹ́ ara ẹni.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ má bínú o. Mò ńṣu lọ́wọ́ ní yàrá funfun ni o. Ẹ káàárọ̀! :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ ṣeun o :). Ẹ sì kú ọdún tuntun.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ologbon lon wa ogbon lo sogbon ologbon lol odey
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
adupẹ o yoruba ọpẹ púpọ lọwọ gbogbo alàtà oniru oniyọ ẹṣe o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láì pariwo, Láì náwó jù, pẹ̀lú isẹ́ ọpọlọ pípé, irú eré tí ó yẹ́ kí àwọn London máa gbé jáde níyì.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Job 8:7 Ipilẹṣẹ rẹ iba tilẹ kere ri, bẹ̃ni igbẹhin rẹ iba pọ̀ si i gidigidi. 👇 Though thy beginning was small, yet thy latter end should greatly increase. #Yoruba #Bible #OOG #God https://t.co/UXkdz7HrJM
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀dá tí ọlọ́run dá kó máa fò ká lófurufú òun ló wá di ẹyẹ àtìmọ́lé fún ọmọ ènìà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
4) Ìyá ràpàtà yàgbẹ̀ẹ́ ràpàtà, ó fi ewé dúdú bòó... Kíni o? 4) A fat woman excretes a big faeces and covers it with a black leave... What is it?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni ebi ń pa ò gbọ́ wàásù. #EsinOro #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ancestors are not serious again. I swear. 🤣🤣🤣☺️. As in won ti gba ibodi 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv… https://t.co/71y1yF9BrW
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọdún tuntun dé, Yáhrọ́bì mo bẹ̀ ọ́ o, ẹkún à sun rìn ma mà gbe bámi o. Ọ̀rọ̀ bí àdanwò, ma mà gbe bámi o."""" #OdunTuntun #2014
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tó gbé ìlù ẹ̀ kọ́ apá ayé ńbáa lùú, ánbọ̀tórí ẹni gbé tirẹ̀ kọ́ igi tó ṣeré lọ. / Translation >>
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aruwo lenu fendo wan pa iro mo mi no o oro boko haramu ti won ni mo so ko ribe rara figbe ta oni ki won ma bu okuta si iresi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #EdeYorubaDunLeti : Oríkì Oníkòyí Fídíò: https://t.co/IpZj9ALl3u |#YorubaRonu #Yoruba #SaturdayThoughts #SaturdayMotivation #…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÀROKÒ / NON VERBAL COMMUNICATION Bí wọ́n bá gé ẹní díẹ̀, fi ráńṣẹ́ sí èèyàn, ó túnmọ̀ sí wípé ará ẹni tí a fi ẹní yìí ráńṣẹ́ sí wà lórí àìsàn. If a piece of mat is sent to someone, it means, the relative of the person is battling with a sickness.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilé koko ntagbe. Olúwa ṣeun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ikilo pataki nipa #Rape ti amosi #ifipabanilopo Iwa ibaje ni ki okunrin abi obirin fi ipa ba arawon lopo. Ko bojumu ra ra. Ti odomobirin abi odomkunrin ba ti so 'Unhunmm' ki olukaluko ya ti kini won bo aso ni o. Tipatipa ko lafin se ere ife. https://t.co/s1GXTlDfqF
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Nitoriwipe, eewọ ni ki ẹnikẹni maa wo kabiyesi l'oju, @user @user @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
9. #Parioweyii B'óbìnrin ò dán ilé ọkọ méjì wò... #Ibeere #Yoruba #EsinOro
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: “@user: Ẹ kú oǹgbẹ o!”awa niyen ooooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pádi ọ̀gẹ̀dẹ̀ (àgbagbà/páráǹtà) . #InYoruba #learnyoruba #Language #Yoruba 🍌 https://t.co/C1AkWXFFCg
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user egbe ke? Owo ero ni won ma n se Faaji irole. E jeki a toju egbe fun sayii :...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: E ku ise ribiribi @user. Odun pupo lati ma a ri tweets ni ede your bank!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
omi làbùwẹ̀ omi làbùmu omi lẹ̀rọ̀ tani jẹ́ bómi ṣọ̀tá kò sẹ́ni jẹ́ bómi ṣọ̀tá rántí láti máa mu omi lóòrèkóòré fún àǹfààní ìlera ara rẹ ́ọjọ́omiàgbáyé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eégún Ẹ̀yọ̀ ni wọ́n ma fi ń ṣe orò ìkẹyìn fún ọba tó bá wàjà ní Ìsàlẹ̀ Èkó (Lagos Island). Ẹ̀yọ̀ náà ni wọ́n fi ń sin Ọba tuntun gun orí ìtẹ́. A tún ń pèé ní , """"""""Adámú Òrìṣà"""""""" Ẹ̀yọ̀ jẹ́ eégún àwọn agbolé kan ní Ìlú Ẹ̀pẹ́, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. https://t.co/Bg65gBfLgH
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ kú ìdìde. Ẹ máa wolẹ̀ o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
wọ́n dá obìrin sí wọn pa ọkùnrin ó ṣe jẹ́ ọkùnrin nìkan ọ̀ràn ńlá rè é ó fẹ́ ìwádìí tó kúnrẹ́rẹ́
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀run kó dẹlẹ̀ fún J.F. Ọdúnjọ, baba náà ṣe bẹbẹ ní ti ẹ̀kọ́ àṣà Yorùbá. @user @user @user https://t.co/nVFCXqkHvj
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oni ni jimoh iwon ba ni ise eni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àti pẹ̀lú wọ́n ní a lè mọ ẹni wọn bí tèlé ni nípasẹ̀ ilà ọwọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ỌỌ̀NI ỌBÀLÙFỌ̀N ÒGBÓGBÓDIRIN, Ọọ̀ni ẹ̀kẹ́rin ní Ilé-Ifẹ̀. Ọọ̀ni Ọbàlùfọ̀n ni ọba tó pẹ́ jù lórí ìtẹ́ ní Ilé-Ifẹ̀ Ọbàlùfọ̀n jẹ́ ọba tó mú ìṣe rírọ irin wá sí Ifẹ̀ Ohun ni wọ́n rọ irin ìbòjú (àwòrán 2) tó gbajúmò yìí ní orúkọ rẹ̀ https://t.co/0ZdlLMNk6c
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Adìyẹ funfun kò mọ ara rẹ̀ lágbà"""" Translation: """"The white chicken does not respect itself."""" #chicken #white #learnyoruba #wisesayings #owe #mondaywisdom #yorubalessons #yoruba #yorubaforbeginners https://t.co/PM9g41XO2W
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹ̀yin Àràbà, ṣé ó dì'gbà tí wọ́n bá ní ilẹ̀ Áràbù ni ẹ ti wá, kí ẹ tó dá sí ọ̀rọ̀ yí.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹní tó bá ṣe ohun tí ẹnìkan ò ṣe ríá á rí ohun tí ẹnìkan ò rí rí whoever does what no one has done will experien
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user omo ale ti o fi owo osi juwe ile baba re. Se ko ba le di gomina lofi fe da ija sile larin omo aje okuta ma mu omi ati Yoruba?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn wo ni a máa ń pè ní """"""""olódo ràbàtà?"""""""" #Ibeere #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjẹ̀bú ló ni ẹ̀wẹ̀ só, Àwórì ló ni kí ti gbé. Ta ló ni ìyokun? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré yìí tí ènìyàn lójú púpọ̀. Àárọ̀ yìí là rí èyí pèlú àwọn òǹwòran lọ́kùnrin àti lóbìnrin àti àwọn ló̩ko̩láya. Bákan náà ni ìsesí àwọ̩n ènìyàn nípa ère yìí. A dúró lẹ́nu ò̩nà gbò̩ngàn sinimá bí àwọn ènìyàn ṣe ń tú jáde. Kò pé tí a rí obìnrin kan tí a fura sí pé ó ń ṣiṣé̩ ni ilé sinimá. Ó bi gbog...
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bukky my sales director. Comitted to not only spreading the word but converting leads to sales. I appreciate you and grateful to you. Thank you Mo dupẹ lọwọ rẹ #ileeko #ileekouk #yoruba #amazingteam https://t.co/j42qWhWtyD
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn to sọwọn nipa àṣà ìdílé lati ọna ti o yàtọ ti won sì gbejade pẹlu òṣèré ti o koju osunwon.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ṣé ìwọ́ mọ̀ pé ẹmu yàtọ̀ sí ògùrọ̀? Ẹmu ni a yọ láti ara igi ọ̀pẹ, ògùrọ̀ ni a mú láti ara igi… https://t.co/0HZssX22Rf
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eni a fe la mo, a ko meni feni denu. Inu jin! Eniyan won, eniyan soro. #Yoruba #IronuAkewi #OlayemiOlatilewa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí ní í ṣe ni tá à á dádé owó orí ní í ṣe ni tá à á tẹ̀pá ìlẹ̀kẹ̀ orí jọ̀wọ́ bá ṣe mi kí n ṣe kòńgẹ́ ire
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ife bi eji owuro latagbala eledumare lo ti san wa, ife to toro minimini latagbala eledumare san wa..........♥ #I…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a bímo kò gbón a ní kó má sàá kú kí ní ńpa omo bí àigbón
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ohun t'ó wá jẹ́ ẹ̀dùn ọkàn fún mi ò ju pé, @user tíí ṣe ọ̀kan lára ohun èlòo @user ńkọ iyán @user kére. #blogger…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èdè Yorùbá L'árinrin l'órí Rédíò @user pẹ̀lú @user moninkanola @user @user E maa gbo Tele wa 👉@user #edelman #ede #yoruba #asoebi #ibadanwedding #asooke… https://t.co/4M6QDMkKQ7
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Bí ọbẹ̀ èso igi ilá bá jẹ́ ọbẹ̀ ilá, tí ọbẹ̀ ilá tí ó ti kó (gbẹ) bá jẹ́ ọbẹ̀ ọ̀rúnlá, kí ni à ń pe ọbẹ̀ ewé ilá? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo fi pàsán na Sùúrùlérè lórí àjà, l'ó bá jábọ́ l'ó bá kú, lóòótọ́ nipé ológbò kì í fẹ̀hìn kan'lẹ̀.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user #yoruba tok say iku enu atiku Loma npa still😈 omugo agba.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ pé ni àwọn ẹ̀gbá sá dé ibi àpáta kan tí wọ́n ba sí abẹ́ẹ rẹ̀ torí ọmọ ogun ọ̀yọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ikú dóró ikú ti pa ọ̀kan lára àwọn ògbóǹtarigi àgbáṣà àti èdè yorùbá lárugẹ bàbá akínwùmí ìṣọ̀lá ti di ẹni ilẹ̀ ó di gb
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èwo nínú gbólóhùn wọ̀nyí ló ní fáwẹ̀lì aránmúpè? A) Fọn B) Fún D) Fín #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ayọ̀ ni mo fẹ o baba ọlọrun ayọ̀ mu ayọ̀ mi kún o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àgbékalẹ̀ ńlá.. . . . Ìtàn tó mọ́pọlọ wá lárà ọ̀tọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣèré tí wọ́n mọ iṣẹ́ wọn níṣẹ́. Ìmọ́lẹ̀ títán sí àtẹ̀yìnwá ọ̀rọ̀ pọ̀ lápọ̀jù dìẹ̀ ṣùgbọ́n ó wuni láti ìbẹ̀rẹ̀ dópin.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
E pele o e kuu igbadun@user: Alákọ̀wé ń bẹ ní #Stonehenge http://t.co/4CxLeTXEar""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Enikan Ooni Tan Layishe Pe Won Tan Ina Fun.@user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èwo nínú aáyán ògbufọ̀ yìí ni ó báa lọ jù: Eng: He is trying to know too much about the matter. a)Ó fẹ́ láti mọ ọ̀rọ̀ yẹn jù b)Ó fẹ́ láti mọ àmọ̀jù ọ̀rọ̀ yẹn d)Ó ń gbìyànjú láti mọ àmọ̀jù ọ̀rọ̀ yẹn e)Ó ń gbìyànjú láti mọ ọ̀rọ̀ yẹn jù #Atelewo #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àyọkà láti inú ìwé tí à ń kà. Fàbú láti ọwọ́ Akínwùmí Oròjídé Ìṣọ̀lá. Kí lẹ rí sọ sí apá òsì. 😂 #Yoruba #AkinwumiIsola #Yorubabooks #zoombookreading https://t.co/Fx9OALmTN4
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ojúmọ́ ire o ìsinmi ayọ̀ la ó máa ṣe o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí Kò dára
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
losogbo wakili dana sun okada araale e lo ba foju bale ejo tolulope
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Tabi ka funni ni oye (information) lori nkan.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn orin àlọ́ nkọ́? ..Ajá ajá o rànmí lẹ́rù..
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
traditional occupations and their modern day equivalents iṣẹ́ àbáláyé àti bákan náà wọn ní aiyé òní gbẹ́nàgbẹ́nà construction engineering àyàn drummer aṣọ híhun fabric production oníṣègùn botanist doctor pharmacologist nurse medical lab science
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e kaabo si orilede wa oun ti oju wa ri ma yen lojojumo won si tan wa je pe ina ti wa bayi odun
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọba Àrà, Ọlọ́tun Ọlọ́jọ Ẹ ṣeun fún oore rírí ọdún tuntun. #OdunTuntun #2014
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
15. Ajá 🐕gbó Ewúrẹ́ 🐐______ Àkùkọ 🐓kọ Àgbébọ̀ 🐔_____ #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oni ni ojo aje ti ede yoruba tin se yoruba monday e maa ba wa kalo a wà lẹ́hìn yín gbain gain bí iké e màlúù
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, O ma se o! Awon agbowo-ori pa Iya Ayo l'Akure, bee opo ni: Obinrin eni… https://t.co/pkOqoZwtd5
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wíwò eré mú mi lọ́ra
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ìmọ́tótó ló lè ṣẹ́gun àrùn gbogbo, ọmọ Èkó ò, ẹ jẹ́ a gbálé gbáta wa kí àyíká wa ó mọ́. Ẹ jáde ṣe #Efaromenta! #Lagos
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ wípé, àwọn Oníṣòwò kéékèèké ní Ilẹ̀ Yorùbá àtijọ́ ni à ń pè ní ALÁÀRÓBỌ̀? Wọ́n ma ń ra ọjà tí wọ́n ma wá tún tà ní kékeré ní ọjà. Àwọn Oníṣòwò yìí má ń ní ṣe pẹ̀lú àwọn ọjà oko (ohun ọ̀gbìn àti ọ̀sìn). Àwọn obìnrin ni wọ́n gba òwò yìí kan.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí Esogban ò bá mọ̀, ẹ bá 'ni wí fún un k'ó máà d'orí ìtàn k'odò, Odùdúwà kì í ṣe Ọọ̀ni, Ọlọ́fin ni, òun ni Ọlọ́fin àkọ́kọ́. #YorubaBenin
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ato se eto ikole gbogboogo ijoba tó ń lọ lọ́wọ́ ni ilu ibadan ìpínlè ọ̀yọ́ tí pèsè ìṣe ẹgbẹ̀rún merin lé laadorin fún àwọn ọmọ nàìjíríà ni agbègbè náà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: Emenike Iyalaya e ....."""" Rọra àwé #idanoripapa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orí mi gbé awo ire kò mí àti àwọn tèmi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e patewo fun ra yin e pegede e fi gbooro jeka
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Já ara rẹ. Ọ̀rọ̀ láti ẹnu ọmọ adú tòótọ́. #Malcolm | #OsuItanAtehinwa https://t.co/UZq1pynMqj
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìṣẹ̀: àfòmọ́ iwájú """"""""ì"""""""" ni a hún pọ̀ mọ́ """"""""ṣẹ̀"""""""" l'ó di = ì-ṣẹ̀. A fi """"""""ṣe"""""""" kún ì-ṣẹ̀, l'ó bá fún wa ní = ìṣẹ̀ṣe. #IseseLagba #Yoruba #Iseseday
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Agbo ni àwọn àgbàlagbà t'ó ti darúgbó kújẹ́ ń mu, tí ẹ̀míi wọn fi gún, tí wọ́n fi ọwọ́ pa ewú, fi erìgì j'obì. #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A i si nibe ni a I ba won da si...Omo oodua ni emi na ooooo....ki eledumare oba oke ko fi oyin si aye wa @user ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ifá kì í nílọ̀, ó ní kí Àgbọnmìrègún ó múra bi obìrin, gbé igi tí a gbẹ́ lére sórí, kí ó fún ọ̀já mọ́yà, kí ó wọ ìkù sọ́rùn ẹsẹ̀. #Gelede
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
omo yoruba melo lo wa ninu ijoba ni ile igbo o fe da idakuda sile ni yen o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pẹ̀lú àwọn ìṣeré tí ó dára nípasẹ̀ Thandie Newton ati Chiwetel Ejiofor, “Yellow Sun” tí ó ní lọ́tọ̀ ń jo tútù.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Gbogbo ibi la ti ń bá ọ, bíi ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀ Ìwọ lónìí, ìwọ lánàá bí ẹkún apọkọjẹ Wàá gbé dúdú, gbé pupa,
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
France gba Senegal ní 1848. Louis Napoleon di ọba ni 1855. #Nigbatiwonde
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: N óò máa tàbọn ní èdèe Gẹ̀ẹ́sì láti ọ̀la lọ, fún ọjọ́ méje gbáko, ní orí aṣàmúlòo @user, tí í ṣe àgbékalẹ̀ẹ @user…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀kan ni wá níwájú elédùmarè ẹ jẹ́ á yéé ya àwọn kan sọ́tọ̀ ré wọn sílẹ̀ gbé àwọn kan ga
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train