text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
@user e se a dupe o gbogbo wa ni a o ri batise rona gbegba ninu osu yii @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣe ògbufọ̀ gbólóhùn ìsàlẹ̀ yìí sí èdè yoòbá pọ́nbélé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user awon ijo tiwantiwa n yen ooo...o ye ki a ma yin awon elere nah#WorldMusicDay | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yoruba integration ìṣọ̀kan àwọn ọmọ oòduà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ọ̀ràn ilẹ̀ níní lóde òní kọjáa sísọ, nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti larí mọ́ ilẹ̀ tí ó jẹ́ wípé àwọn abulẹ̀ṣowó tà fún ẹni méjì t… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Stop attacking me. Meal plan ti forí ṣọ́pọ́n🤦🏾♀️ https://t.co/arNCz1VvPM | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Adventure of Robin Hood, Cisco Kid, Hop Along, Cassidy abbl gbajúmọ̀ láàárín àwọn ọmọdé lórí ẹ̀rọ náà ní 1959-1964. Ní 1962, ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ náà gbé ètò Èkó oríṣi bíi, ìmọ̀ ohun tó ń ṣẹlẹ̀, tí ọ̀gbẹ́ni Christopher Kọ́ládé darí rẹ̀. Ètò òmíràn, Ministry of | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òlè ò ráyé wá o, ibi ọmọlọ́mọ ni alápámáṣiṣẹ́ já gbà. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìwà lẹwà ènìyàn ló dífá fún Tacha lọ́jọ́ tón tìkọ̀lé Instagram lọsí #BBNaija wọ́n ní kó rúbọ ìwà, Tacha kọ̀. Kàkàbẹ́ẹ̀ ófi ọmún ya tattoo ó nfi perfume wẹ bí omi. Àsẹ̀yìnwa àsẹ̀yìnbọ̀ Ẹlẹgbọn Àgbà lé kúrò ni #BBNaija19 bí ẹní lé ajà. Tún ìwà rẹ ṣe ọ̀rẹ́ mi https://t.co/omGWWkFw6p | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èlé àti èrè okòwò ẹrú (£2.5m) ni a fi kọ́ ojú-irin àkọ́kọ́ ní Cuba ní 1834, Britain l'ó sì kó owó yìí sílẹ̀ fún Spain. #OIANUK | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#iroyin, #yoruba, Ope o! Abenugan ile asofin tilu oyinbo de, lo ba n pin Gala ati Tii… https://t.co/bCzNyqBkky | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Saleh nípé lójú àwọn kò sí ìyàtọ̀ láàrín àgbà àti ọmọdé | #Bokoharam #BringBackOurGirls @user http://t.co/FSSz6fmtok | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
júdasi olè o pá jesu jẹ olè orin | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àyájọ́ ìfẹ́ ti tún ré kọjá l'ọ́dúnnìí. Àmọ́ má jẹ́ kí ìfẹ́ tán láàrin wa nígbà kankan Ọlọ́run wa. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
akéréfinúṣọgbọ́n akọ́nilọ́ràn bí ìyekan ẹni ọ̀rúnmìlà ló ń jẹ́ bẹ́ẹ̀okitiripì a jí pa ọjọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àjọ̀dún wo rè é ní Ọ̀ṣun, Ilé-Ifẹ̀? #Nigeria #Yoruba > @user http://t.co/Ta7MFYYKyK | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
o fi enu ba adebola je | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹbọ ni wọ́n ní kó ṣe èṣù ló sọ alábahun àpáta | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user !aba oh. K'ara o le oh. Ajinde ara yio maa je oh! Ki Oba oke pa ona wa mo l'ose yio. Amin. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
11. Ọfà fún tafàtafà Igbà fún ọ̀kọ̀pẹ Ada fún amọ̀kòkò ____ fún apẹja #Ibeere #Yoruba #IseIbile | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojo = coward (ojo ni Òjó - Òjó is a coward) #InYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alákàn l'ó kọ́ ilée tiẹ̀; bẹ́ẹ̀ ni kò fi t'omi ṣe. Sọ ìtumọ̀ òwe yìí. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3G, 4G, ní báyìí 5G ti ń kanlẹ̀kùn. Wọ́n ti ní àrùn jẹjẹrẹ ọpọlọ yóò lékún sí i nítorí agbára èyí tí ó ń bọ̀ lọ́nà dẹ̀dẹ̀ yìí peléke. Àfàìmọ̀ kí ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ẹ̀rọ àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ó máà kásẹ̀ ayé nílẹ̀. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí ni òrófó kí ni òfóró | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àparò kan ò ga jù kan lọ, à fi èyí tó bá gun orí ebè. / One patridge isn't taller than another except the one on a mound. [Discrimination is vanity: we are more alike than we are different; envy no one, but be humble.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Good happy Eid Fitr to all Muslims around the world. May Allah accept our Ramadan fasts and reward everyone abundantly. A kí gbogbo Mùsùlùmí káàkiri àgbáyé, kú Ọdún Ìtúnu Àwẹ̀. Allah yóò gba àwẹ̀ oníkálukú, yóò sì san èrè àwẹ̀ náà fún wa. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kanye west ń kọrin níbi ayẹyẹ ọlọ́dọọdún iléọnà ti ọnà ìgbàlódé ní garden benefit new york city ọjọ́ oṣù karùnún àwòrán láti ọwọ́ọ jason persse cc bysa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
In Yorùbá iyì means worth/value http://t.co/BRAjjApO3Q | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bóyá ilé ojú omi ni ká pe òmíì. Ẹ wo bí wọ́n ṣe kọ́ èyí ní alájàmẹ́ta, tí wọ́n sì dárà sí i pẹ̀lú. http://t.co/ZCuvz560qQ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ibi ti daddy mi o de ma de be ma tu koja ibi ti mummy mi o de ma de be ma tu koja iykyk️ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn Oníròyìn, onímọ̀-ẹ̀rọ, akèdè ẹ̀rọ ayárabíàṣá kọ̀mpútà jákèjádò ti péjọ láti jíròrò lórí ìlọsíwájú, àǹfààní, òfin àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. #InternetFreedomAfrica https://t.co/tI20fGbPMi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
láyé àtijọ́ àwọn àwòràwọ̀ í ma á na ọ̀pá àṣẹ sí àtẹ́lẹwọ́ wọ́n á ki ifá kedere sì ni ohun gbogbo nípa ẹnítọ̀hún lá á hàn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré ṣíṣe nlá, isatunkọ to dara ti o se pelu ìtàn tó dára, eré kíkọ náà dára pẹlú, ni àkótán, iṣẹ nla láti ọwọ Genevieve Nnaji. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
omo kekere o kin dagba loju obi e ̀bá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
10. Ènìyàn pupa ni 'apọ́nbéporẹ́' Ènìyàn dúdú ni 'adúmáradán' Ènìyàn gíga ni_____________ #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♠ Mo pinnu láti ṣe bẹbẹ ju ti àtẹ̀yìn wá lọ. Ki Olúwa ó ràn mí ṣe. Àmín • #IpinnuOdunTuntun #yobamoodua | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Alafia #AlafiaAtiIsokanFunGbogboEniyan #Yoruba #Langbasa #Lagos #Nigerian #African 👏🏼🙌👏🏼🙌👏🏼 Alafia ati isokan fun gbogbo eniyan https://t.co/4KdbaCGVtC | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
sisí yẹmí ẹ ká alẹ́ o ẹ sì kú iṣẹ́ takuntakun o olúwa á wà pẹ̀lúu wa àmín | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ogún - 20 Ògùn - Drug Ògùn - State Ògùn - Charm Òógùn - Sweat Ògún - Iron Ó gúun - Stab Ogun - War Ogún - Property Ó gùún - Climb Ó gùn - Long #Yoruba https://t.co/pAmb7PsnKk | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ ń ṣe bẹ́ẹ̀ ń gbógun ti ọjà, pa ọmọdé, obìnrin lọ́jọ́ àjọ̀dún tàbí ayẹyẹ pàtàkì. #Ogbomoso | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Irú jígí wo ni ọ́? #FathersDay | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tí wọ́n wà ní ìgbẹ́ìn láàárín ọjọ́ mélòó kan àwọn ọmọ ẹ̀gbá pa ẹgbẹ̀ta ajẹ́lẹ̀ ní ẹ̀gbá nígbà tí aláàfin gbọ́ èyí ó rán àwọn ọmọ ogun láti ọ̀yọ́ ẹ̀gbádò àti ìbàràpàá lọ sí ẹ̀gbá kí wọ́n lọ jẹ ẹ̀gbá run ṣùgbọ́n nígbà tìí kakanfò baálẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♫ Aráyé ẹ má pe ẹnìkan lọ́lẹ mọ́n, kádàrá lowó ♫♪ #AyinlaAdegeto #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Bẹ́ẹ̀ ni baba. Mo ti kàn sí wọn ṣùgbọ́n ó dàbí pé wọn ò rí i. Màá tún ṣọwọ́ sí wọn. Ẹ ṣé mo dúpẹ́ o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aṣìwí ò tó àṣìsọ tó dífá fún ìyá ọba kan níjọ́ kíní àná tó pe ara rẹ̀ ní ìyá ọ̀bọ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọjọ́ kẹta ni ọjọ́ Ògún; Oṣoosì. Ọjọ́ kẹrin sì ni fún òòṣà Ṣàǹgó; Ọya. #yoruba #calendar | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹni òjò pa, tí àrá kò pa, kó má a dúpẹ́. / Whoever got beaten by rain but wasn't struck by lightning should be thankfu… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìjọba wa yìí oadarí aṣojú àti aṣòfin wa gbogbo ọdún titun la wà ẹ fi ìfẹ́ bá wa ṣe pọ̀ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ó yẹ kí iléiṣẹ́ aládàáni ó lọ́wọ́ ńnú ètò ẹ̀kọ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Iroyin tó te @user lọ́wọ́ sọ pé @user àti àwọn méjì miran ti @user mú tí wọn sì fojú bale ejo lọ́jọ́ru yóò tún sún oorun ọjọ́ kejì lọgba ẹ̀wọ̀n, https://t.co/Tjqv0Dy6WE | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó ti wà bẹ́ẹ̀ lọ́jọ́ t'ó ti pẹ́. Olóògbé bàbá Alfredo Darrington Bowman tí àwọn èèyàn mọ̀ sí """"""""Dr. Sebi"""""""" ti ilé iṣẹ́ ìwádìí USHA ní America ṣe àfihàn àwọn oúnjẹ ikú wọ̀nyí. Kódà, ọ̀ràn náà só síni lẹ́nu, ó tún buyọ̀ sí i. Nítorí owó 😔 https://t.co/GRstj5uMCt | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Akaba yìí kan náà ni ó jágbọ́n idà tí ó mú tó láti bẹ́ orí ọ̀tá péú lọ́wọ́ kan bí èlé ṣe ń bẹ ajá Ògún. #OgunDahomeyAtiEgba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àwa lomo abéòkúta ìlú rere ìlú olólá ibè náá bí àwon akínbò sí ègbá omo lísàbí e máá de ònà dègbá | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé o mọ̀ pé Ọba Adéfúnmi Adéjuyìgbé ni Ọba ìletò Ọ̀yọ́túnjí ní America? Kábíèsí o! #SouthCarolina #Yoruba #Oyo http://t.co/nHV8EkyBVq | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nbo lààrẹ ìlú aláàárẹ̀ wà? """"""""@user: Ni bo laare wa? http://t.co/hdRdRybiJo @user @user @user @user"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user @user @user Awon omo alatakiti Boko Haram du adota omo elesin kiristi ni Ipinle Borno - http://t.… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ayodeji ni emi n je.Oniroyin ni mi.Mo n'igbagbo pe ojoola rere mbe fun orile ede Naijiria.Ki Olorun bukun fun orile ed… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ṣé ara yín ti yá gágá? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user eni ti oloyun #ibeere #QnA #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ́ k'á tẹpẹlẹ mọ́ ètò ìdàgbàsókè fún ìlú olókìkí yìí kí ògo wa máà wọmi, ẹ jẹ́ a fa ara wa sókè. #IjobaWaKala #Nigeria @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìfàkókòṣ'òfò míràn. . . . Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìranù ní Netflix, inú mí dùn pé ọ̀fẹ́ ni, nkò san owó fún àkójọpọ̀ burúkú yii. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
in yorùbá ọwọ́ is hand apá = arm ìka = finger ateleowo palm èékánná is nail | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Amin ase lola eledua""""""""@user: @user — baba mi..... Aran lao ma da oooo, Ao ni da ran!"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ere to ń ru ènìyàn nínú tó sì fà nílẹ̀ | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: #KOKOINUIWEIROYIN: APO IKOWOSI ILE OKERE, EGBE OSELU PDP PE FUN FIFI OWO SIKUN OFIN MU ASIWAJU BOLA AHMED TINUBU | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ere apanilẹ́rìn-ín lórí Kérésìmesì. . . Ere yìí kún fún ẹ̀rín àríntàkìtì. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ilẹ̀ tutù. A kú atura o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Um pouquinho dele 🎶 nosso @user ♥️ . . Olùbọ̀riṣà láti BRÀSÍL ń ya oríkì 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba… https://t.co/lWXirNi5HQ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♫ à ń jáde lọ lòní elédùmarè ♫ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Yorùbá ló ni Nija ká gbé èdè wa lá ruge #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo kí baba wa alàgbà nelson mandela kú ọjọ́ ìbí kẹrìnléláàádọ́rùnún àpẹrẹ nlá ni ẹ jẹ́ fún gbogbo wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Irú ẹ̀fọ́ kan báyìí tó ma ń sun omi púpọ̀ jáde lára bí a bá sè é tán ni a mọ̀ sí ebòlò. #Ebolo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: A sọmọ ni Șódé, ọmọ lọ sí àjò ó dé. A sọmọ ni Șóbọ̀, ọmọ t'àjòbọ̀. A wá sọmọ ni Șórìnlọ, ọmọ rìnlọ kòdé mọ. Tani kò ṣàìmọ̀ p… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ tún wo èyí. http://t.co/Eu6dpu9B | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú iṣẹ́ òní o. Iṣẹ́ẹ wa ò ní di ìṣẹ́ mọ́ wa lọ́wọ́ o láṣẹ Elédùmarè Akotun. #Yoruba #Bond929fm | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oriki mi ni Ayoka,abiso mi ni IYABODE abi mi ni adugbo kan ti an pe ni lawanson ni odun die seyin,eku irole,oodua a gbe wa #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ipade di @user nibi ajodun @user Ire o! #SoYoruba #GboYoruba #KaYoruba #KoYoruba #Yoruba #YorubaLakotun #FreedomPark #LagosBooksandArtsFestival #asayoruba #litiresoYoruba https://t.co/NHzhmmzcUk | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bì òkánjúwà bà dàgbà tán sebí olè lón tèlegbogbo won lón kólé eni elénieni eléniòkan àkóbí èkejì àbúrò | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ará ọ̀run kì í fọhùn bí ará ayé nítorí bí òòṣà ṣe ń sọ̀rọ̀ bí ẹni tó dí imú sọ̀rọ̀ la fi ń pè é ní adíimú adímú | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo fẹ́ràn àwọn fíìmù ayé àtijọ́ bíi èyí. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
awon onigbeseonijekujeoninakuna apa gbèsè orílẹ̀ tó kù díẹ̀ ká san tán láíyé ọbásanjọ́ ni wọ́n ti | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbogbo ohun tó ń múnú bí wa nípa ẹlòmíràn lè mú wa ní kíkún nípa ara wa(irú ẹni tí a jẹ́)"""""""". - Carl Jung #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/ujzz43kPeR | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ìrèké ò ní ibùdó; ibi gbogbo ló gba alágbára. / Sugarcane has no specific place of refuge; every situation suits a di… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹkáàárọ̀ o. Ẹ kú àsùnjí. Ọlọ́run Ọba Atóbijùlọ ni agbára àti ìgbẹ́kẹ̀lé wa lọ́jọ́ òní. #ekaaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ire ni tiwa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú òwúrọ̀ o. Ọjọ́ ayọ̀ ni o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: O káre lai, sugbọn *púpọ* ni o @user: Ope pupu fun @user @user @user @user @user ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí 9 sọ àṣà #Germany, kò síyàtọ̀ pẹ̀lú ti wa! #Rome yí àṣà àti ìlànà, ó sì mú mìíràn wá láti fi gba àgbárá àti láti gbàlú. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
O mu ní mólè. . Zainab ṣe dára dára gẹ́gẹ́ be Sylvia. O je kí ń ma pe òùngbẹ eré yìí si. Nínú gbogbo ká lọ ká bọ̀ ṣe ni mo le jù mọ ẹ̀rọ àgbéléwò yii. Níse ni mo ranjú mọ́ ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán mi mo sì ríi pé ọkàn mí fà sí Sylvia. Ìfanimọ́ra rẹ̀ pọ́ọ̀ jù, ṣùgbọ́n eré síse rè tayo jù béè l... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ibi tí mo rìn dé báyìí http://t.co/AnwyWJHL | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo kí ẹ̀yin ẹ̀dá náà. Ènìyan laṣọ mi. Ẹkú ojúmọ́. Ire la ó rí o. #ekaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
parí òwe yìí ìtóò tí ò fara lu igi kíni ìtóò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣe ti ọba. Ká fọwọ́ wẹwọ́, ṣ'óhun lọ́wọ́ fi ń mọ́. Ọba kò ṣe tán láti fi ọwọ́ wọ́nú. Ìlàrí tó rán lọ sí ibi ìpàdé náà fi hàn, ohun tí Aláàfin ní lọ́kàn. Bí wọ́n ti pe ìlàrí ọba, kí ó lè jábọ́ ohun tí wọ́n jọ pinu pọ́ sìí, orúkọ Káfilégbọin tí ìlàrí náà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èyí yí ni òsì tí Ọwá nínú eré náà | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
àsè yí sàmódún o ẹ kú ọdún titun oooo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni #matter? Kí ni #Molecule? Kí ni #Physics? Kí ni #Atom? Kí ló ń jẹ́ #Science? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ogún pínpín bí baálé ilé bá pa ipò dà àwọn ẹbí ma pín ogún rẹ̀ ní ọ̀nà yìí ìdí igi ọ̀nà yìí ni àwọn ẹbí fi ma ń pín ogún olóògbé láàárín àwọn ìyàwó rẹ̀ tí olóògbé bá ní ju ìyàwó kan lọ wọn ma pín ogún rẹ̀ bákan náà láàárín oye ìyàwó tó bá ní | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àti ọ̀kánjúwà ni wọ́n fi ń gba ohun lọ́wọ́ àwọn ará ẹ̀gbá bí àìsìnmi ọ̀tẹ̀ tí ń ró kolá kolá bíi bàtá ní ọ̀yọ́ arákùnrin kan ní ẹ̀gbá tí ń ṣe líṣàbi láti ẹ̀gbá aláké bẹ̀rẹ̀ si ní kó àwọn ọmọ ẹ̀gbá jọ ní ìkọ̀kọ̀ láti ja ìjà ìgbara lọ́wọ́ ọ̀yọ́ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oṣù Ọ̀pẹ tí a wọ̀ yìí oṣù ire ni fúnmi àti olùkù mi gbogbo, mo ti rí i, yóò sì rí bẹ́ẹ̀ lọ́lá Ọba Oníbú-ọrẹ. #OdunNloSopinoBabaRere | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
nijeria yi ti gbo gbo wa ni ko ma gbodo baje tori kosibo miran to ale lo ajo ole dabi ile eje ka sowopo ka fimo sokan gbe ke mi gbe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.