text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
RT @user: @user Ope fun Oba Edumare fun ase yori Obama. E kaaro eyin eniyan mi. Se dada le ji? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Èwo ni ọ̀rọ̀ pọ́n-na inú gbólóhùn yìí? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Inú mi dùn kọjá ààlà :)) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Obìnrin tí à ń pè ní èémí ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀ àti eré ìfẹ́ papọ̀ mọ́ àwọn wàhálà tó jẹ mọ́ àìní ìtọ́jú òbí àti èpè àtìdílé wá. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user eba was so fun awon #IStandwithBuhari wipe Ile epo ni mekunu un duro si lati igba tiedi Aare Ema kabunkun o https://t.co/fBaeU2w147 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní kété tí mo wọlé, wọ́n kí mi káàbọ̀, wọ́n bu omi fún mi mu. #Ogbomoso | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà láti ọdún 1999 sí ọdún 2003, Dókítà Olufẹmi Okunrounmu, bàbá àti ìyá wọn bí wọn ní ọjọ kọkọnla, oṣù kẹjọ, ọdún 1939. #EdeYorubaDunLeti #yoruba #Nigeria #tuesdayvibes #tuesdaymood #TuesdayMorning #History #TodayInHistory #todayisprin https://t.co/vl6JFIK7Ob | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user O fe pada si ese aro #yoruba #ManUtd #MUNTOT | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣágo ń bú ìgò, èèbó Jaap@user, BrendaBleek kọ Iré fún Ire, @user ọmọ Yoòbá kọ Oódua fún O'òduà. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Ninu Ile Yoruba,Musulumi ati Christiani gbe igbe Alafia ati Irorun. Ko si ija, ade ni ife ara wa. 😎😎😎 #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù náà dára mó sì gbádùn rẹ,mo rí òun tí mo gb'ọ̀kán le nigba tí Chief Daddy fí ma parí. Awọn òṣeré ṣé iṣẹ́ takuntakun àti wípé fíìmù náà pa ni l'ẹrin. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Nǹkan tí ìwọ yóó ṣe fún orílẹ̀-èdèe rẹ ni kí o rò, má ro ohun tí orílẹ̀-èdè rẹ yó ṣe fún ọ. #Ise #Agbe #yoruba #yobamoodua #Nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n á ní """"""""kí l'ó pa á?!"""""""". Kò kú sí 'hun tún ń pa 'ni lẹ́hìn ikú, sábàbí l'ó yàtọ̀ọ̀tọ̀. Ẹni ire nikú ń mú lọ, aṣebi ń kọ́! #IkuOdaju | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àbá tó bá jẹ́ òótọ́ ni pé ẹ̀sìn lẹ̀ ń jà fún kílódé tí ẹ fi ń pa mùsùlùmú aláìṣẹ̀ àti ọmọ́dé àti àgbà | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ilu ati nje oka kato mu eko yanga. ogbomoso ogbomojugun #TweetinYoruba #TweetInYorubaDay | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kini a mo ti a fee so o""""""""@user: Tanmo kowaso, nikiya kiya kowaso ni we we, kowaso ni wara nsesa kowaso @user @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èyin Ojúlówó Omo Yorùbá o, ę kú isé o, 😁👏🏿.. ìdáhún sí ìbéèrè wa rè o. 😘 #Yorùbá #folktales #ÀàlóYorùbá #Yorùbádùn #wevaluemoral #Yorùbáculture #Besttribeever.… https://t.co/GmOiDxhnmF | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
se ife tomati ni sa iran yoruba kan feran alaafia ati irepo ju ohunkohun lo ni | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ ti mọ̀ bí ẹní m'owó ohun tó fẹ́ ṣẹlẹ̀ ń wákàtí yìí. #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀pọ̀ òjò ti rọ̀ ilẹ̀ ọ̀gẹ́rẹ́ sì ti fà á mu | | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A kìí gbà'kàkà lọ́wọ́ akítì. Kò ṣ'ẹni tó lè gba ire mi. Ọlọ́run ló fi fún mi o jàre. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eṣinṣin tí kò bá gbọ́ ìkìlọ̀ ló ńbá ọ̀gẹ̀dẹ̀ wọ ẹnu ọ̀bọ. / Only a disobedient housefly accompanies (a bite of) banana into the monkey's mouth. [Moderation is it; lack of self-control can be costly.] #Yoruba #proverb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
HOW WELL DO YOU KNOW YORÙBÁ LAND/ BÁWO NI O ṢE MỌ ILẸ̀ YORÙBÁ SÍ? 1) What is the name of the tourist site that, Ìbàdàn people say: you don't know Ìbàdàn, if you have not been there? 1) kíni orúkọ ibi tí àwọn ará Ìbàdàn ma ń sọ wípé, èèyàn ò mọ̀ Ìbàdàn, tí kò bá dé ibẹ̀? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Pẹ̀lú gbogbo ariwo #jamb nípa ìdánwò orí ayélujára, wọn ò sí lóríi @user | Àbí ẹ mọ ìdìmú wọn? | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹnu ẹnu làwọn olóríi wa fi ń ṣe é láti iye ijọ́ yìí. Ọ̀la ni ma pa á, ònìí ni ma pa á, wọn ò tíì pa á. #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bọ́mọdé bá ń dalẹ̀ kí ó má ṣe da ògún ọ̀rọ̀ ògún léèwọ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbà mélòó la ń lò láyé. Rere ló pé ìkà ò pé. Ẹ jẹ́ ká ṣe rere o. Àt'ore àt'ìkà, ìdjájọ́ fẹ́rẹ̀ẹ́ dé. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ḿ bomirin àti kí o ń ṣiṣẹ́ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Yèyé Ọmọ́táyọ̀ Ọmọ́tọ̀ṣọ́ #NTDC náà gba àwọn ìyá níyànjú láti fún ọmọ lọ́mú dáadáa. #YEYE_IyaNiWura http://t.co/uY1V9g0d48 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Iwa ika kope ara mi,ema danwo, iwa ika kope ara mi,raara koda. Ire ape,ika ape,ile lo mo eni tio te oun pe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lati gbadun #Iroyin ti ko lafiwe, #Eto lorisirisi ati #Ipolowooja ti ko gani lara ni Ede #Yoruba, #Hausa ati #Igbo, e maa tetisi #Bond929fm. Bond FM, 92.9, ore araalu laje. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹrù ẹgba àtòrí yìí ni ọ̀rúnmìlà gbé dání ní ìrìnàjò rẹ̀ sọ́run | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
This is good Ìfẹ́. Kú akitiyan 💪 https://t.co/JdEUov1Oxk | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àtẹ Ẹ̀yà-Ara Ẹ̀dá Ọmọ Ènìyàn - Ọmọ Yoòbá @user #smashwords https://t.co/vPwLI6OjZ5 #Yorubabook #Anatomy #Morphology | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user # o see gbere, Oodua a gbe e, ori e a kanke. O ni ba araye fowo tii. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A kú oríre ti àṣeyọrí, a tún gba ife ẹ̀yẹ àgbáyé bọ́ọ̀lù àwọn ẹyin-níí-dàkùkọ lẹ́ẹ̀karùn-ún. #U17worldcup #Nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Irú iṣẹ́ tí kò ni ìmọ̀ ṣíṣe àwòrán nìí. Ó yà ni lẹnu pé wọ́n mú u jẹ, nígbàtí ọ ba ní eré tí kò dára tí ó mú ni kúrò ní fíìmù. Maṣ̣e fi àkókò rẹ ṣòfò | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Gistas mi ọ̀wọ́n, A kúu ọdún, a kúu ìyèdún o. Ẹ̀mí a ṣe ọpọ ẹ. #eidmubarak2019 . DM me for my Sallah meat is important. Serious inquiries only please. . . #lifeofagista #ondo #yoruba #makingyoulaughseriously… https://t.co/1QkvOC2nT0 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ gbàmí ẹja tútù ni àwọn wọ̀nyí ń kó jẹ bí ẹní jẹ̀bà o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
odù ifá wo nìyí | | | | | | | | | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user OJUMỌ ALAYỌ LOMỌ GBOGBO WA. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbẹ̀rẹ̀ fíìmù yí kàn dàbí ìgbà tí ènìyàn bá kó ẹyẹlé pọ̀ mọ́ adìyẹ ni.. . Kò sí àlàyé nípa bí Laila kàn ṣe fara hàn. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Èmi nìkan tán. https://t.co/oRUKHbNLWV | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
opolo yi ma wa si rin o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn wo ni Yoòbá ń pé ní alábaraméjì? #ibeere #QnA #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ere loloja nje labo oja. Gbogbo wa la o jere. #FuelSubsidy #Epo145 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àpèmọ́raẹni làá pe tèmídire. Tèmídire o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn yẹn àti gbogbo rògbòdìyàn inú rẹ̀ ni mo fẹ́ràn.. . Àwọn apá kọ̀ọ̀kan bí mi nínú ṣùgbọ́n ìgbẹ̀yìn rẹ̀ rẹwà.. . A ní láti gbé ìgbésẹ̀ tí a fẹ́ fún ayé wa nítorí enì kankan kò ní báwa gbé e.. . Ìșọwọ́ múra òșèré tó léwájú wù mí àti irú irun tí ó ṣe. Ẹwà àmútọ̀runwá máa ń dára. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Impeachmentì bá wo? Ẹ se ure! Kílóń jẹ́ #impeachment. Ẹ se ure! ♫ #ElemureOgunyemi | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀kan nínú àwọn fíìmù tí ó ṣòro jù tí mo wò rí. Google ṣeé tí wọ́n ṣe yíyá rẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Èyí jẹ́ ìtàn ti ìrora, ìdádúró àti ìrètí, ṣùgbọ́n nígbàmíì ó jẹ́ àìrójú. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Òtútù yìí pọ̀ :( http://t.co/I3S5Gdzn | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
rákòrò | rákòò | rá =► to crawl oṣù méje ni pópóọlá rákòò pópóọlá began to crawl at months | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
answel wong ni olórí ikọ̀ tó dá oṣù ìtàn adúláwọ̀ sílẹ̀ ní ọdún ní uk fún ìrántí ọmọ adú | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní gbogbo ilẹ̀ #Yoruba, enìkan ṣoṣo ni kì í dọ̀-bá-ilẹ̀ (dọ̀bálẹ̀) fún ọba, ta ni ẹni náà? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àìsàn oun gbogbo láti àì mọ̀ ìtàn so sí gbígbé jáde eré tí ò bójú mu sí àì mọ̀ eré ṣe | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
àgbà tó ròfọ́ ìkà ọmọ rẹ̀ á jẹ níbẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òsè yí á sàn wá sí rere! K'ámáà kó ìríra omo enìkejì wá! Wonderful and rewarding week to u all! #owe #onnahrocks #hush #sgit #castleandcastle #amajoche #nollywood #sweet #london #yoruba #yorubademon @user Glitz Event… https://t.co/04hbKjHBcv | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
What occupation is old Ìbàdàn known for? Clue: it is in their eulogy Kíni iṣẹ́ tí àwọn ará Ìbàdàn àtijọ́ yàn láàyò? Ìtọ́nisọ́nà: ó wà nínú Oríkì wọn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
likes e se gan o apapo omo yoruba yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oba ọlọ́wọ́ gbọgbọrọ tín yọ ọmọ rẹ̀ nínú ewu. Ọ̀gbàgbà tí ngbani lọ́wọ́ bìlísì. #Olódùmarè #yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
awon aliankanse ni fi esin ke wo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... tí ó sì ń yọ́rẹ̀ ta ẹrú láti gba ìbọn Lọ́wọ́ àwọn oníṣòwò Portugal àti Brazil. Kí ìsinmi baà lè wà ní ìlú, Ọba Akítóyé ní kí Ẹfúnroyè fi ìlú sílẹ̀, nígbà tí ìjà ṣẹlẹ̀ láàárín Ẹfúnroyè àti àwọn olówò ẹrú yòókù. Ní ìgbà tí Ọba Akítóyé wàjà, | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ gbọ́'yìí o. Orin aládùn --> #AwaOTushOh ~ http://t.co/8t5ZxITH #Dobale ~ http://t.co/3ZVj8iMA | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kére o kére o ọ̀gbẹ́ni alákọ̀wé yorùbá ti ń pín owo iyebíye fún ẹnikẹ́ni tí yóò dìbò fún un ní | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni t'ó jẹ̀bi yóò san owó ìtanràn fún aláre, àwọn ògbó yóò pa obì, aláre yóò gba awẹ́ obì kan, ẹlẹ́bi yóò gba awẹ́ kejì. #IdajoNileYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ife ondaye, ibi ojumo ti nmo wa. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Màá fẹ́ fún ní máàkì méje nínu mẹ́wàá ṣùgbọ́n…. . Bí wọ́n kàn ṣe parí rẹ̀ láì lórí láì níìdí ba sinimá náà jẹ́. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
kàká kí a mu omi inú ẹ̀rọ amúomitutù tí ó ń fa ìpalára a ò ṣe padà sí omi inú àmù tí ò ṣe ara ní nǹkankan | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Agbẹ́jẹ́ gbà wọ́n là á ní kí á pa á ní pánsá. #EsinOro🐎 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
In Yorùbá ọmọ òrúkàn means orphanage child #Yoruba #Yorubaword http://t.co/NElmhRaPAp | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣíṣe ti kò dára pẹ̀lú awọn òṣèré àìní ìjìnlẹ̀ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Oshey @user on this 1 you're speaking up now sir gbayi ✊✊ #EndSARS #EndSWAT #EndPoliceBrutalityinNigeria #EndBadGov… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbọ́ ọ̀ràn ni ó di ìgbọràn/ìgbọ́ràn, kí ló di 'agbárí'? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... alágbẹ̀dẹ, atagbòkun, alágbàá, ẹlẹ́tu ìbọn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ jantirẹrẹ ló rí jájẹ ń'núu okòwò ẹrúu nì. | #TransAtlanticSlaveTrade #OwoEru | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mountain in Yoruba is òkè gigá while hill is òkè kékéré and valley is àfonifojì, http://t.co/4bGLoJcY | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
naijiria yìí ti gbogbo wa ni kò mà gbọdọ̀ bàjẹ́ torí kòsí ibòmíràn tí a lè lọ àfi amẹrika àti úróòpù | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
22,000 owó ẹyọ ni ọ̀daràn ẹyẹ tí í musàn yóò san fún abẹ́rí. #IdajoNileYoruba #Asa #Yoruba https://t.co/JATKyPEPY9 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹní bá ríbi ṣu á dáwọ́ tẹlẹ̀ á fẹju ranran | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ̀yin tí ẹ̀ ń pe igi tí a fi ń fọyín ní pákò ẹ jẹ́ kí n sọ fún un yín wípé oríṣi orín kan ni à ń pè ní pákò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Iye ko ni won npe ni orun ma wo? @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
9• Òkè òkun ni a bíi sí, a sọ ọ́ ní Adéwálé. Ọmọ wo ni à ń sọ ní Tòkunbọ̀ nílẹ̀ẹ Yoòbá? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Omo to je igbadun gbagbe ile woni oso apo iya re koni .Omo ale yoruba ni o Femi Adeshina.A total disgrace to the yoruba rac… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
gbogbo wa la máa kú ọmọ yobá bá aṣíwájú ìlú èkó kẹ́dùn ikú ìyáa wọ́n àbíbátù mọ́gàjí ẹ̀yìn ìyá á dáa o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìrẹsì lake yìí ṣé kò ní gbéwó lórí bó bá yá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí rè é? Níbo la ti ń ríi? #Yorùbá http://t.co/mtzhMItmit | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: ọdún yìí á bá wa lárá mu o, a ò sì ní sìse lọ́lá ọba Olúwa. A kú ayọ̀ ọdún tuntun! @user @user @user ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ibi gbogbo lo gba alagbara ole nikan ni aaye o gba e je ki a le imele jina ki a tera mo ise wa ki a le di eni ti aye n wari fun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
💪💪💪⭐🌟🌠⭐⭐⭐⭐⭐🌠⭐⭐⭐Boy! Omoluabi! Omo karo o ji ire! Mimi aiye o ni mi e! Eni ba fe mu oni e! Ola ni wan ma mu! Gbe gbe okin gbe si oko! Ayo, alafia, arijo, ariyo ni ti e ati awon ayanfe e! @user oju oni ti e! Ara o no ni e! Ijamba oni de ba e! Aase! https://t.co/umctFG2cpC | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user bẹ́ẹ̀ ni, ọ̀pọ̀ orúkọ awo nínú Ifá l'ó jẹ́ orúkọ ìnagijẹ. Orúkọ ìnagijẹ awo ní í bẹ̀rẹ̀ àwọn odù kan. Irú ni ti Pàlàbà awo.. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù tí o dára,rí o sí je ki o ṣe èmi, gbìyànjú láti mọ ibí tí yíò darí si | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Àjẹ́ ké lánàá, ọmọ kú lónìí.. #WhoKilledDeleGiwa | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ara wọn. Aláàfin Òfiràn gba ìlú tí wọ́n ń pè ní Kúsù, ìlú tó wà ní bíi àádọ́ta máílì sí Ìwọ̀ oòrùn Ọ̀yọ́ Ilé, níbi tó gbé fi ṣe ibùgbé. Aláàfin Òfiràn wàjà ní Kúsù. Ọmọ rẹ̀, Egúnojú ló jẹ Aláàfin titun. Aláàfin Egúnojú ṣí ìtẹ́ Ọ̀yọ́ lọ sí Ṣakí fún ìgbà díẹ̀, | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Awon onimo nipa oju ojo kilo wipe Sandy yoo si tun ja fun bii wakati merinlelogun sii | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn Faransé a sì ti ṣe oúnjẹ l'ẹ́ṣọ̀ọ́ kàlákìní. Ṣé jíjẹ náà làá jẹ ẹ́. A kò le gbé e kọ́ araògiri. A ò sì lè wọ̀ ọ́ bí èwù. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbogbo ohun tí ó yí fíìmù yí ka ni ìfi tipátipá pani lẹ́rìn-ín lọ́nà tí kò rajaja. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
♪ Ọdún yìí, á sàn wá sí ire, á sàn wá sí ayọ̀, á sàn wá sí gbogbo nǹkan tí èèyàn fi ń láyọ̀ ♪ » #Oduntuntun2015 @user #Nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ogbeni GEJ ni wipe oun o ti raye tiwon,pe oro iyawo oun se koko ju rakatia yen lo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÌBEJÌ: Òrìṣà ọmọ méjì tí wọ́n bí ní ìgbà kan náà ÈGÚNGÚN: Òrìṣà tí àwọn Yorùbá fi ń ṣe ìrántí àwọn èèyàn wọn tó ti kú, tí wọ́n wà ní ọ̀run. ÒGÚN: Òrìṣà ogun, ọdẹ, àgbẹ́dẹ, irin | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... Máà k'órí burúkú wá bá mi ò. Ó ṣ'àárọ̀ Mọ́ńdè o! 🎵 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.