text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Aláké Òdí, ló ṣe ilé de baba rẹ̀ lórí ipò ọba. Asẹ̀ ni ó jọba lẹ́hìn tí Aláké Òdí wàjà. Asẹ̀ bí Ikin. Ikin bí ìbejì, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Ọbátúapá àti Ọ̀pálápá. Ní àsìkò tí Ọbátúapá yóò jọba, ó ní wọ́n ní láti fi Kẹ́hìndé òhun náà jọba. Ọbátúapá jẹ Arẹ̀sà Adú
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
jimoh oloyin oluwa a gba adura waamin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oro olori North Korea dabi omo kekere to ri ibon he, to fi pa eku leekan to wa ro wipe gbogbo nkan ti ohun ba ti ri ni oun le maa koju e si
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eni ti ojo ti a ya si le la ti ma soro nipa aarun jedo jedo lo se ayewo ko de gba ajesara le ni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eni ti o ba mo nipa asa ati ise ile yorubabo ti wu ko kere to ko ni sai farahan
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aláàfin Aólẹ̀ wí fún Baṣọ̀run kí ó pèsè Kùránì náà. Ṣùgbọ́n, Baṣọ̀run sọ wípé, òhun ò mọ ibi tí Kùránì náà gbé wà. Ni inú bá bí Aólẹ̀, ló bá ké pè sí àwọn Alálẹ̀, tí í ṣe Ṣàǹgó, láti wá Kùránì náà jáde fún òhun, bí èèyàn ò bá ní wa. Àrá bá bẹ̀rẹ̀ sí ní lu àwọn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A pa ẹmọ́ lóko ilà, a jù ú sí ọ̀kẹ́ ìlasa; ilé ẹmọ́ lẹmọ́ lọ. #Owe #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
baba nla ere ni gej fi re wa lara loni e maa wo iro bantabanta bayii lenu olori orileede
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Igba o lo bi orere.... lo difa fun @user https://t.co/LrWFxwS8H0
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Apa keji 🎼🎼🥁🎹🎺🎸🎼🎷🎺🎸🥁 Aje kun iya ni'oje, aje kun iya ni'oje, eni ti o t' eni no, t'on de na de ni, aje kun iya ni'oje https://t.co/qUyz8WN3tZ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: If, male - Baba ọkọ Female - Iya ọkọ. #Yoruba https://t.co/2RflAgXcsv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Imọ-ẹrọ @user wa ni iṣawari fun gbigbe owo ailewu. Ṣayẹwo awọn iroyin lati wa idi ti a fi gbagbọ ninu #XRP. Awọn ilana jijo #global #dance #challenge #fun #Africa #Yoruba https://t.co/HiO4OQEfWk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ṣé ẹ máa ráàyè darapọ̀ mọ́n wa fún #tweetYoruba baba? --> http://t.co/52eEZngdRg
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àgbà ò sí ìlú bàjẹ́, Áwò kú, a gbàgbé ìlànà tí ó là á lẹ̀, a ò rántí bí ìṣàgbẹ̀ ti fa orílẹ̀ èdè Nàìjíríà sókè níjọ́hun àná. #IjoOle
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
new edit ẹrú kan ló mú ni bú igba ẹrú one slave causes the abuse of two hundred oth
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nípa ti ọ̀rọ oúnjẹ nílùú mi. A ní ẹranko àti òwú, ṣùgbọ́n ọmọ ẹlẹ́ran wa ti ń jẹ egun, aláṣọ wa ti ń wọ àkísà. #OmiInira57
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user :) èdè mélòó ni ẹ gbọ́? Ṣé ó ju mẹ́ta lọ?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
B’ópé títí, akólòlò yó pe """"""""baba"""""""" Lodifa fun akede ijoba Nigeria Lai Mohammed oni ki a gba kamu, wipe @user un se ise ninu iyewu @user https://t.co/DcmCVJxIgI
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ wi fun Twita @user ki o dakun dabọ gbọ ti ọmọ yoruba o ;). #twitterYoruba #TweetYoruba #Yoruba @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bẹ́ẹ̀ ni a kúkú ń kí wọn kúuṣẹ́ takuntakun naa èdùmàrè á ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣe takuntakun sí i
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user alafia ni ooooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo kórira sinimá yìí gan-an ni ò
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user, emi ase pupo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user gbogbo ilu ni o. Arun tii se ogoji nii se oodunrun
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àșejù pọ̀jú nínú eré yìí. Èyí ló jẹ́ kí wọ́n șișẹ́ kárakára láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ẹ kóbọn wọlé o ọmọ ìyá a máa para wọn bí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nítorí ire ni ẹyẹlé máa ń fà wá ní a fi ní tọ́tún tòsì lẹyẹlé fi ń kóre wọ̀lú ẹyẹ ire ni a ka ẹyẹlé sí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìfàkókò ṣò fò. . . Fíìmù yìí burú . . ó burú gan-an
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user ẹ̀yin náà wà níbí? Ẹ kú iṣẹ́ o! @user #MAYAAwards2016
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré àgbéléwò àti orin #Nigeria lóríi ayélujára @user #smwlagos #Nollywood http://t.co/KJwDfcNauA
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní dídájú, ọ̀kan lára eré tí ó bani lérù tí wón ṣe
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
eku ayeye ojo ibi eni igba odun odun kan ni hbd egbon
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó máa wu ẹ̀yin ganan tí ẹ kì í ṣe awo kíákíá lẹ máa fẹ́ẹ́ darapọ̀ mọ́ wa kò sóhun tí à ń gbà lọ́wọ́ àwọn ọmọ awo tó papòdà ju ẹran àgùtàn lọ ẹ̀jẹ́ nìyẹn téèyàn gbọdọ̀ san nígbà tó bá fẹ́ẹ́ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ awo tó bá ṣẹlẹ̀ pé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user eranko inu àwòrán yìí ni a n pe ni Ikoko lede Yoruba. #Ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú orí ire
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""""""""""@user: #Hubert Ògúnǹdé spoke fluent English. Yet, he neva let go his Afrikan heritage. A true Ọmọ Yorùbá. #RIP"""""""""""""""" beni,om…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àdìsá kẹ̀ ta ló fún yín lóríkì àràbarà yìí orúkọ oríkì káyọ̀dé nù n o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àgbọ̣dọ̀ wò. . . . Eré tó dára. Seye ní àwọn iwa tí ó jẹ́ pẹ́ gbogbo obìnrin ni yóò fẹ́ ẹ…Tí ó bà sí fé wo ǹkan pẹ̀lú ti obìnrin, màá gbà ọ́ níyànjú kí o wo èleyí. Eré tó bójúmu fún èèyàn láti wò pẹ̀lú ẹbí ni.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user: @user toba fenu kan nko?"""" Ọ̀run lẹ̀rọ̀ ni, ẹ bu iyọ̀ sí ìgbín kí ẹ ríi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Awon Ilaje ati Ikale lati Ipinle Ondo. Naijeriya. □ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #hausa #igbo #yoruba #oodua #oduduwa #ondo #oyo #lagos… https://t.co/GTxQl3NL9I
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èdè a máa jọra ṣá àgbákò ìjàmbá ogun ni ewu ní yorùbá ewúrẹ́ ni ewu lédèe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìmọ̀ràn yìí inú wa dùn sí ìdí tí a fi ń kọ kíkọ ní èdè gèésì àti yorùbá ni wípé àwọn tí kìí ṣe ọmọ yorùbá náà lè ní àǹfààní láti kọ́ ohun kan tàbí èkejì nípa ilẹ̀ yorùbá a ma ń kọ kíkọ wa ni yorùbá àti gẹ̀ẹ́sì
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
... oníṣẹ́-abẹ, àti ọ̀gọ̀rọ̀ tí ó ń lo irin níbi iṣẹ́ gbọdọ̀ júbà Ògún. Torí gbogbo ohun irin, t'Ògún ni #OsuOgun https://t.co/G1a4mplGvS
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
o ò ní àkàṣù ò ńpata sí ẹ̀fọ́ èyí nií pé nígbà tí kò sí ẹ̀bà àmàlà fúfú ìrẹsì a á ṣe máa ṣèto ata fi sẹ̀fọ́ kí la ó fi jẹ̀fọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ajo to mojuto idanwo ile iwe giga ti kede atona awon akeko uni je poly sije http
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
wọn lọ sí oko ṣùgbọ́n bí ogun bá wà àwọn obìnrin ma wà láàárín ìlú níbi tí àbò ma ti wà fún wọn orísun niara sudarkasa where women work a study of yorùbá women in the marketplace and in the home the university of michigan abala
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọba ti wàjà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò s̩e é fo̩wó̩s̩ò̩yà rárá pé ó dára láti wò.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ǹjẹ́ o mọ̀ wípé olórin nì Carlos Santana ki #Sango ń'nú orin rẹ̀ tí ó pe àkólé ẹ̀ ní """"""""Hannibal""""""""? #Yoruba http://t.co/Sy1ARUAiMb
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ìmọ̀ ò pin
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó jẹ́ eré tí ó níse pẹ̀lú ǹkan tó o Kári ayé.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ìgbádùn rẹpẹtẹ ni o. Ẹni l'éèyàn ní mọsàn kìí mu kíkan. A mọ̀'yàn níbẹ̀ ni o :))
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
daddy egbo wan ni e o ti san owo awon osise fun be osu merin be ede gba owo epo robi fun ondo se iwa omoluabi yin re
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Ó ga jù! Alàgbà Tẹju ẹ̀yin náà báwọn wọ'ṣọ àlà. Ó mà dùn mí pé n kò sí níbẹ̀ o.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user sebi eniyan mi ni won. Awon ti mo soro won fun yin. Awon wonyii gan-angan ni mo n so nipa won. Eniyan laso mi #Appr…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìbò ṣì ń lọ, àwọn ọmọ #Nigeria rere gbé ẹ̀rọ-amúnáwá sílẹ̀ #Ibo2015 http://t.co/y5gczXNX3v
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user @user Aku iyedun, Oluwa a fi ire kin ire o. Ase
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eku asiko yio awa omo yooba lapapo, amama ri ohun rere barea she oo. Niger oni baje oo! #TweetYoruba https://t.co/bbfVMo8t7t
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#UNILAG náà lóun ti dúró nílé tó. #ASUU #200BN
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Otutu ke? Sebi iyawo yin wa ni tosi. Ale ebere de RT """"""""@user: Ago márùn péré ló lù àmọ́ ilẹ̀ ti yáa sáré ṣú. Òtútù …
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àìtètè mú olè, olè á mú olóko.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọlayẹmi oniroyin isreal si n feje awon ara palestine wa bi sango
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kòríni-kò-mọni (aago 🕓 sí 🕔) ìdájí ni àsìkò tí ilẹ̀ kò ì tíì mọ́, tí sánmà ṣì dúdú. Ó ṣòro láti rí ojú ènìyàn lásìkò yìí. Bí a kò bá sí rí ojú ẹni, yóò nira láti mọ ẹni tí a rí.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo ebí wọ́n ní ikú kì í pa ọmọ ẹtà lójúran àmọ́ àwọn apẹrannpakúpa tí ó kún igbó lóde òní ti pa ẹtà tán nígbó nítorí
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọniyì 1. The child is honour. (Ọmọniyì) 2. The child has honour/worth/value. (Ọmọ́níyì) https://t.co/nTXL7uxxVQ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Happy 6th birthday in advance to the original son of the land 🎉🎉 29.03 ọmọ ògún ò rọ'kin, àgbẹ̀dẹ ò'rọ bàbà ọmọ kúlódò…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìròyìn langbasa lórí lórí ìkànnì pẹ̀lú sweet fm abeokuta
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn Yorùbá gbàgbọ́ wípé, tí ọmọ bá kọ́kọ́ hu eyín òkè, àṣẹ wà ní ẹnu ọmọ náà. Nítorí náà, wọ́n ma ń kọ́ àwọn ọmọ náà láti gba àdúrà, dípò pé kí wọ́n ma ṣẹ́ èpè.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilorin mesu jamba...... eni ti ori oselu Ilorin to ko sa..... @user ti fi oju yin ri mabo. Oya @user agbo to feyin rin lo..
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀yin àjínigbé! Ẹ ò ṣe lọ máa jí àwọn jẹgúdújẹra, àwòdì jẹun èpè sanra olóṣèlúu wa gbé, ẹ óò rí owó t'ó t'ówó gbà. Àmọ̀ràn ni. Ire o!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú ti ìlú wa. Ẹ dẹ̀ kú ti Ebola tí ò fẹ́ kí a máa f'aranura, f'arakanra, k'á báraa wa ṣe, k'á kórajọ ... #YesKe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user o gba ojo iku niyen
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó gajù. . . . Fíìmù yìí ti jẹ́ kí n yí ọkàn mi padà nípa nǹkan tó dára. Ere tó fakọyọ ni. Ere yìí fà nílẹ̀ díẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ ṣùgbọ́n ó wuyì láti wò. Ìrántí àwọn abala tó ti kọjá jẹ́ kí ìparí ere náà túnbọ̀ dùn nítorí pé gbogbo nǹkan kàn ń ṣẹlẹ̀ papọ̀ ni.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
nílẹ̀ yorùbá bí alágbára aláṣẹ tàbí onípò láàrín ìlú bá ṣe àṣemáṣe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Genevieve Nnaji kan ẹsẹ mọlẹ ninu awọn.oludari olóyè. Kò já kulẹ nínú iṣẹ àkọkọ rẹ. Eré lion heart je agbọdọ wo, bi o se polongo ibi Nollywood káàkiri àgbáyé.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Oluwa duro laelae fa'bada nitori pe, eyi o wu awi ti oluwa lase #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àlejò t'ó f'òru wọ̀lú; igídá ni yóò jẹ. #EsinOro🐎 #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òní ni àpérò àwọn ọ̀dọ́ tí ó dá lé ìṣẹ̀ṣe ní akodì ọ̀sẹ́ méjì ọjà ọba ìbàdàn níbi tí a ó ti máa tú àwọn ohun tí ó ta kó
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kàyéfì ajinigbe jí ajinigbe gbé
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
d àrọ̀nì olóògùn ìkà ni àrọ̀nì lójú ayée rẹ̀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ibi à gbé làá ṣe; bí a bá dé ìlú adẹ́tẹ̀ a di ìkúùkù. / We adopt the way of life of where we live; in the land of lepe…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
come mondaythe lagos conductors will start singingobalende obalende wòle pelu mask é ni o oni gloves ma wòle o fòwò ko to gba change è rona o ran yan o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ló ń ṣẹlẹ̀ ń'Bàdàn náà, ẹ wí í mi! #Ibadanmajamaja
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ire lo pe ika osuwon
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Just have to love #IFÁWẸ̀MÍMỌ́ #YORUBA #tiwantiwa #Alkebulan #Ọ̀ṣun #YèèyéÒṣun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Wọ́n ní kò sí ohun t'ó dára rárá ń'nú ti wa. A ò mọ Ọlọ́run, a ò lẹ́sìn :( @user @user @user @user…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gbogbo ẹran tí sùúrù bá sè tí kò rọ̀; Ọlọ́run ń bínú sí i ni. 🍖🍗 .......................................................…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo ẹni ń da ilẹ̀ kiri àdúgbò onídọ̀tí tí n dọ̀tíi èkó ẹ̀yin lọ́ ń bá wí o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àsìkò ti tó láti yan obìnrin sípò ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà! Kí àwọn ìyá wa báwa tún ìlú ṣe! #Naija #2015
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
o ma se o ijamba moto gbemi awon onisowo marun loja oluode nilu osogbo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọmọ ìyáa antelope; deer ní í ṣe.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ayọ̀ àti àláfíà ni nbẹ n'nú ọkàn mi lónìí. #:)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ gbọ́ náà, àwọn kan sọ wípé ojúṣe ọkọ àtaya ni láti gbọ́únjẹ, wípé kì í ṣe iṣẹ́ obìnrin, kí lẹ rí sọ sí i? #IleOkoIleEko
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ta ni yoòbá ń pè ní èṣù lẹ́yìn ìbejì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nọ́líwuùdù tún gbé ìṣe wọn dé.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ọ̀gbẹni Amos Ọlátunjí Pópóọlá jẹ́ ọkan nínú àwọn márùn-ún to yege jùlọ nínú ìdíje ẹ̀bùn ìwé kíkọ Ẹgbẹ́ Àtẹ́lẹwọ́ fún iṣẹ́…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#OroAmoye Enikan kii je awa de,opo enia nii je jomoo,agbajo owo la fi soya. E je ki a fowo sowo po lati gbe orileede wa goke agba.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ ṣé púpọ̀ púpọ̀. A gbádùn yín gidi #ThinkOyoRoadTrip
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kíni ìwé yìí mú yín rántí nípa iléìwé alàkọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ what does this book remind you of about your primary school days
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user @user Bí mo bá purọ́ kí òkun gbé mi lọ, kí ọ̀sá wà mí bọ̀, kí Olódùmarè dá mi lẹ́san, n kò kúndùn bọ̀ti mìíràn ju @user lọ, àwọn olùkù mi mọ ìyẹn dájú. Kò gbọdọ̀ jẹ́ èmi, mo máa túṣu désàlẹ̀ ìkòkò. #EtoOnibaara #consumerright
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train