text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
kiise pe agö naa bi ko se pe ibëru fojo nii se wa tan feku tan fë fi ëmi rë elë
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo bu mo o da nje e bu mo o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A kàn ń gbọ́ ẹni yìí kó mílíọ̀nù sílẹ̀, tọ̀hún gbé bílíọ̀nù kalẹ̀, pẹ̀lú 'ẹ̀, a ò r' ẹ́jẹ̀ a ò r'ómi ra. Wọ́n sé wa mọ́lé, a kò rí ìnawọ́sí ó kéré ó pọ̀ láti ọ̀dọ̀ ìjọba, àwọn tí wọ́n jẹ́ akúṣẹ̀ẹ́ tí wọ́n ní yóò rí oúnjẹ táṣẹ́rẹ́ gbà kò rí.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé iléifẹ̀ ti lo onírúurú sáà sẹ́yìn kí ó tó kan ifẹ̀ òní otù ifẹ̀ ifẹ̀ oòdáyé ifẹ̀ oòrè ifẹ̀ oòyèlagbò àdàpé ifẹ̀ oòtólú ifẹ̀ ọọ̀ni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹgbọ̀rọ = the young of animals (ẹgbọ̀rọ kìnnìún yìí ń bú ramúramù ⏩ this lion cub is roaring) #InYoruba #learnyoruba #language https://t.co/44rPJaovBN
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn yorùbá á ma lo ẹní fún ìjókòó ní inú tàbí iwájú ilé tàbí láti gba àlejò wọ́n sì lè tẹ sí ilẹ̀ fún iṣẹ́ ṣíṣe ní abẹ́ igi tí atẹ́gùn ń rọ́ kẹ̀ kẹ̀ lábẹ́ rẹ̀ wọ́n lè tẹ́lẹ̀ ẹní sí abẹ́ rẹ̀ láti gba atẹ́gùn tí wọ́n sì ma sinmi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Trinidad àti Tobago jẹ́ àkọ́kọ́ nínú àwọn orílẹ̀-èdè ní àgbáyé tí yóò ya ọjọ́ sọ́tọ̀ láti sààmi ìfòpin sí òwò ẹrú, àmọ́ lẹ́yìn-in 34 ọdún tí ìsinmi àpapọ̀ náà fi ẹsẹ̀múlẹ̀ àti ọdún 185 lẹ́yìn-in ... https://t.co/jzUlJiIa3c #Yoruba #OkowoEru #Ominira
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
in yorùbá ìwé ìgbanisíṣẹ́ is appointment letter
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ni ile ayé ti ìyá ti n fi ọmọ rẹ̀ bọrítí ẹ̀gbọ́n ti n fi àbúrò rẹ̀ dájọ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Beeni, amoo ki enu wa ma ko adura.""""""""@user: @user @user Alawurabi o ki nfi ebi kankan pa wa. Awa eda la n…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni tó ńbẹ̀rù àti ṣubú, àti dìde á nira fún un. / Whoever is scared of falling will find rising pretty tough. [Nothing ventured, nothing gained; be bullish; be open to taking calculated risks.]~@user #Yoruba #proverb #SARSMUSTEND #EndPoliceBrutality
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn kan ò mọ ìyàtọ̀ ń'nú ọpọlọ́, lénte, kọ̀nkọ̀ àti àkèré, ọmọ ìyá ni wọ́n, wọ́n jọra síbẹ̀ wọ́n yàtọ̀. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user iwo ti an wo aparo bi ka fi dala.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: Ejowo mio mo.. Ewoni? RT @user: Èwo ń'nú ìwọ̀nyí ni ègúsí; 1) Aro 2) Ìtóò 3) Rere #Ibeere #Yoruba"""" Ìtóò ni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilà ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ọ àti àwòrán jẹ́ méjì ń'nú ìwífún tí ó yẹ kí a fojú sí. Àwòrán, ní pàtàkì, lè yọ́ mínrín so ìṣàmúlò tí o fẹ́ jẹ́ ó dá wà pọ̀. Èyí wọ́pọ̀ ní ibùdó ẹni-tó-ń-wá-ọkọ-wá-aya àti àkáùntì onímọ̀.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹnìkan kì í jẹ kí ìlú fẹ̀ one person eating satisfyingly never translates to a towns progress common good is
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ gbìyànjú láti máa béèrè ọ̀nà kí ẹ má ba à ṣìnà #languagelearning #yoruba #iyil2019 #indigenouslanguages https://t.co/iUt0w2HVoL
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo kí ọmọdé mo kí àgbà. Káraóle o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
5. Èwo nínú mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ni gbólóhùn mìíràn fún ọ̀gbẹ̀rì? A. Olojò B. Awo D. Múgù #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọjọ́ Ẹtì. A ò ní wá nǹkan tì, a ò sì ní di àwátì. Àṣetì ò ní jẹ́ ti wa, a ò ní ṣe é tì. #Amin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ha wahala wa o yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni yoruba tv
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♪ ÌṢẸ̀ṢE dọwọ́ ẹ̀yin baba wa! Ẹ̀ máà jẹ́ ó bàjẹ́ o, ẹ̀sìn'ṢẸ̀ṢE dọwọ́ ẹ̀yin baba wa""""""""- lóhùn Àṣàbí Ọ̀jẹ̀. #IseseDay https://t.co/qgNiIxGQv6
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Inú ìṣẹ̀ṣẹ lẹ̀sìn ìgbàlódé-lonígbà-ńlò ti yá àṣà àti ìṣe, wo ìlànà ẹ̀sìn Christian àti Islam fínífíní, wà á bá ìṣẹ̀ṣẹ, ó pọ̀ ṣúà. #IseseDay
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Nje O mo? Sunday-Monday ni ede Yoruba Aiku Aje Iṣegun Ọjọru Ọjọbọ/Alamisi Ẹti/Jimọ Abamẹta #TweetinYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ba se n se niyen. #SoundPoetry. E ma gbadun e lo.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo pade @user losan yii mo feran imura ati isoro won #akefestival
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jẹ ki ohun gbogbo ti o li ẹmi ki o yìn Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Oluwa. #ORIN_DAFIDI 150,6. #Yoruba #Psalms """"""""Que todos os seres vivos louvem ao Eterno! Louvado seja o SENHOR!"""""""" #Salmo 150, 6.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èyí tí ó ṣe ìwúrí jù ní ibẹ̀ ni wípé, oye oyè tí olóyè kan bá jẹ ni oye Iyùn tí ó ma gbà. Tí ó bá jẹ oyè mẹ́wàá, Iyùn mẹ́wàá ni ó ma gbà. Ó wá kú sí olóyè náà lọ́wọ́, láti lo oye Iyùn tí ó bá wù ń sí ọwọ́ àti ọrùn, bí ó bá ń jáde.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user @user Aiye le: Obirin loyun fun oko re, lo ba dana si ile won pelu oun ati oko re ninu e http://t.…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọwọ́ epo ni ọmọ aráyé ńbá ni lá, wọn ò jẹ́ bá 'ni láwọ́ ẹ̀jẹ̀. Bí àṣà #Abobaku bá ṣì ń bẹ, a jẹ́ wípé ọ̀dàlẹ̀ n'ìdílé #AbobakuOoni Ifẹ̀.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwa ò ní táwọ́ ná. A kò ní wò níbi ẹgbẹ́ ti ń náwó. Atare kì í ṣe láì máà di tirẹ̀ lọ́kẹ̀ẹ́ ẹ̀kún, àpòo ṣáṣamùrá kì í sì í gbẹ. Àpòo wa yóò máa ga gọbọi ni, ọwọ́ọ wa ò ní kan ìsàlẹ̀ àpò. Lágbára Ọba Aláṣẹ. Àṣẹ́ ti gùn ún! #iwure #OjoAje #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
'Irinajo ọmọ orukan' láti ọwọ́ Julianah Adeleke (with English translation) https://t.co/i5vYmQgyZo via @user #yoruba #writing
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìbáṣepọ̀ wo ló wà láàárín ọ̀rọ̀ ìkórìíra àti ẹ̀rọalátagbà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ǹjẹ́ o mọ̀ wípé ọdúnun ni òyìnbóo gẹ̀ẹ́sì láti wọ ilẹ̀ẹ ìbíní
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user se nkan ti e feran ko niyen? #TweetInYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user I don't pay attention to sienna drivers too, igi ewédú ò ní wó pa wá 🤷🏽‍♀️
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó yá ẹ jẹ́ k'á ṣe kiní yẹn? #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #Language
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù to yanilenu. . Itan to rewa, siso daadaa ati sise daadaa. Gbogbo nkan lati ibi ti won ti se ere, kikun oju, awon osere, ede ati fifihan asa dara.. . Ku ise nKunle Afolayan
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Awon oyinbo ko wahala ba Banki GTB ni London
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user @user Ę da kun se oni ni kan la fi aye gbaa #TweetinYo…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
E kaale o. Se ko ti pe mi ju bayii? Emi naa fe farapo mo awon ebi, ara ati ore ti won nfi #yoruba se ede ori Twitter loni oh? #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àsopò eré tí ó tíi burú jù.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Àmín àṣẹ. Ire làá bá pàdé. A ò ní k'àgbákò.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré yìí gùn s̩ùgbón kò dùn. Kódà, orin ti wó̩n ń ko̩ ní abé̩lè̩ gan-an kò wúlò. Kò tilè̩ si ́nǹkankan tí a lè s̩e láti s̩àtúns̩e eré yìí.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ORIN ÌDÁRAYA - LÁBẸ̀ ÌGI ÒROMBO: http://t.co/5MM590sa1x via @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀kọ́ dára púpọ̀ ẹ̀kọ́ lo layé tawà yìí sẹ́. Ẹ̀kọ́ lo ń gbéni dépò gíga, ẹ̀kọ́ lo ń gbéni dépò ọlà..."""" #ChildrensDay2013 #Nigeria #UBE
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní ayé àtijọ́ bí aláàfin ọ̀yọ́ bá wàjà àwọn ọmọ kábíèsí pátá lọ́kùnrin ni yóò gba aṣọ agbádá ńlá kan olorì kan àti ẹrú kan
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
koni gbe awa ati ebi ara ati ore lo oo ojo atura lo ma je fun wa ase edumare
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Odami loju pe kii se iru Yooba kanaa ni Oodua & Sango so ni'gba ti won. Ayipada maan de ba ede gege b ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣọ̀ún ikúmóyèdé àjò ṣọ̀ún kẹ́ta ló gbé ìjàpá yìí wá nígbà tí ó ń bọ̀ láti ojú oògùn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gbé | Gbè | Gbẹ | Gbe | Gbẹ́ • #InYoruba #learn #Yoruba #language https://t.co/FKfzBCGo8t
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""Jide ,o da mi loju pe, o ti bura lati ma wa sile mi !""""""""RT @user: Túmọ̀ (cont) https://t.co/rTC7af87j2
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
4) Ìyá ràpàtà yàgbẹ̀ẹ́ ràpàtà, ó fi ewé dúdú bòó... Kíni o? 4) A fat woman excretes a big faeces and covers it with a black leave... What is it?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a jíire oo ara wa yá gágá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Olorun ni kan l'o ye o... “@user: Àfi kí Elédùà gba ògo, torí òhun nìkan lọ̀rọ̀ #MH370 yìí yé. @user @user”
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tí ìṣẹ́ ò bá jẹ́ ká sọ òdodo àìṣòdodo kò ní jẹ́ ká bọ́ lọ́wọ́ ìṣẹ́ if fear of poverty makes us lie lying will keep us entrenched in poverty as well honesty pays dishonest lifestyle does exact hefty fees at the end
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Kí Ó ṣàánú gbogbo wa o. Ọlọ́run á gbọ́ àdúrà wa o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
DURO lori 'leri Kristi Oba mi Maa korin iyin Re tit' aiyeraiye Emi y'all o korin ogo Re li orun Duro lori 'leri Olorun #Yoruba #HymnFriday
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
“@user: @user @user A nse opolopo Ipaye Lori oro yi pelu awon Omo ile iwe ati oluko won.” #LASU
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èyí tí ó kù kí 2015 ó yọ́ tán, igbe láabi ò ní kọ́gun s'ọ́dẹ̀dẹ̀ wa, mùkúlúmùkẹ ìhó ìdùnnú lá máa dún ńlé kówá o. Ẹ ṣ'àmìn àdúrà!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Bi o ba ni idi obinrin o ki n je kumolu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo ki gbogbo wa barika jimo oni o emi a se opolopo amin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yóò kí í aya ọdẹ náà, tí yóò sì ma bá tìrẹ lọ. Idi èyí ni wípé, ẹyin ojú ọdẹ àti ìyàwó ọdẹ òmíràn ò gbọdọ̀ kan ara wọn, débi wípé ọdẹ wọn ma bá ara wọn sùn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Owo olopaa te Abayomi to n jale l'Ondo, bee pasito lo pera e - Alaroye
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀yà iṣu kan ni ọ̀dùnkún, kí là wọn ẹ̀yà iṣu mìíràn tí o mọ̀? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àkànnàmọ̀gbò kì í pa ọdún jẹ ✔️ Àkàlàmàgbò kì í pa ọdún jẹ ❌ Àṣìpa òwe ni 'àkàlàmàgbò kì í pa ọdún jẹ', 'àkànnàmọ̀gbò kì í…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Falana gbo ti e...... Oto leni ti a fi egba no.........
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eniyan se kole nm fun sultan ijoba sokoto ko se daradara fa e ba ni wadi oro yi wo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ko kuku si iyato ninu ati oruko ikan unje asinwin oruko ekeji unje digbolugi ema wo wan bi ere ori itage
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A kì í sọ òkò sí ẹyẹ tó ńwá ọ̀nà àti fò. / Do not throw stones at a bird that seeks to fly away. [Act in wisdom: do no…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ògún l'ó fi ìmọ̀ tẹkinọ́lọ́jì irin ṣíṣe kọ́ àwọn ìran wa, gbogbo ohun èlò tí ó jẹ́ irin, àti àwọn t'ó ń fi irin ṣíṣẹ́, jẹ́ t'Ògún. #OsuOgun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
From alamoja.yoruba @user, à ń kí i yín pé ẹ kú ọdún o, a kú ìyèdún. Àṣèyí ṣàmọ̀dún láṣẹ Èdùmàrè https://t.co/mLwMzfHILS
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user olodumare a fun wa ni ominira, nitori wipe inu omi inira ni ilu yi wa bayi!!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user gẹ́lẹ́ ni, jẹgúdújẹrá alájẹìwẹ̀hìn. Bámúbámú ni mo yó n ò mọ̀ pé ebi ń pa ọmọ ẹnìkánànkan #StellaOduahGate
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user LASU fi kun owo ti won Gbade lowo Ikobayo Eko fun idagbasoke ile Eko giga naa.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Erin ẹgàn-an Myanmar ń bẹ ń'nú ewu, àwọn adẹ́mìí légbodò kò jẹ́ kí wọn ó gbáyé, erin kan lọ́sẹ̀ kan ni wọ́n ń pa. https://t.co/X4JGxmieCt #Yoruba #Erin🐘
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àyájọ́ òní ni a bí gbajúgbajà ìkòtó akọrin jùjúu nì sunday adéníyì ìṣọ̀lá adégẹ̀yẹ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí sunny adé sáyé kára ó le o bàbá ẹsẹ̀ mẹ́ta ni ti àgbó igba ọdún láyé ení ni kí ẹ fi ṣe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Yoruba #proverb: Orúkọ ní ń kọ́ ṣaájú kí oyè ó tó tẹ̀lée 'The name precedes the title.' - What does this mean to you?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé Ilé-Ifẹ̀ ti lo onírúurú sáà sẹ́yìn kí ó tó kan Ifẹ̀ òní? * Otù Ifẹ̀ * Ifẹ̀ Oòdáyé * Ifẹ̀ Oòrè * Ifẹ̀ Oòyèlagbò Àdàpé * Ifẹ̀ Oòtólú * Ifẹ̀ Ọọ̀ni #IleIfe #Ife #Iwase #Yoruba https://t.co/rOYrijEVl7
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Toò, kò jẹ́ bó ti jẹ́. Ọjọ́ kan péré ni à ń tọrọ rẹ̀ fún ìṣẹ̀ṣe. Àbọ̀ ọ̀rọ̀ là ń sọ f'Ọ́mọlúàbí. Ojúmọ́ Ire! #Yoruba #Iseseday #August20
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ile Ẹ̀kọ́ @user : Abeokuta Grammar School, London Film. School,. Ile ìṣe to dá silẹ : Mainframe àti Television production. https://t.co/zgmhw1Av5j
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ gbódò là ló fi ń gbọ́mọ pọ̀n. Ẹjá b'ómi rẹ́ l'ó fi ń d'ọlọ́mọ yọyọ. Nítorí náà, mo di ọ̀gẹ̀dẹ̀, mo là bẹẹrẹ, mo di ẹja, mo ní ọ̀wọ̀ rere yọyọ lẹ́yìn. #iwure #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo wa la ní èèwọ̀, ó kàn dun ni ni, a ò kà á sí mọ́ torí ọ̀làjú, ó sì ń kó bá wa. #eewo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo ti ji ka iwe apileko ogbeni @user mo rerin arintakiti ni http://t.co/FH0YFDjZ. E ku ise opolo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#np Ise Agbe Titled: Ogbin ni akuro https://t.co/5MWSdAg85K #yoruba #wednesdaythoughts #agriculture https://t.co/hWV8os3dup
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tẹ́ba tẹ̀lé mi, èmi na á tèle yín o, ìyẹn ni wípé “I follow back” 😂
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kọ́jọ́dá ọjọ́ dá ọjọ́ sunwọ̀n oòrùn ayọ̀ wa yóò máa tàn káyé láràn kalẹ́ kò ní sí ìhámọ́ lọ́dún tuntun àṣeyè tálákàn ń ṣepo ni tia lọ́dún yìí ọdún á jọ gbogbo wa la ó ṣàmọ́dún àkànnàmàgbò kò ní pa ọdún jẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user 🇳🇬🇨🇫🌍Ashura ni iṣọtẹ ti olododo ati ominira pẹlu nọmba kekere, igbagbọ ati ifẹ nla si awọn alade aafin ati aw…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Pápàpá, ọ̀pin ọ̀sẹ̀ tún wọlé dé. Ọlọ́run Ọba ò kọ̀ wá sílẹ̀. Ó ń tì wá lẹ́hìn ni. Ọpẹ́ ló yẹ Olúwa. #OlorunSeun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: 2. Èwo ni ọ̀rọ̀ aṣàpèjúwe nínú gbólóhùn yìí : Simisọ́lá sùn gbalaja sórí ibùsùn #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
latari aisan owoori aregbesola ti banki merin pa losogbo tolulope
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọge Ṣàṣá kan fẹ́ ṣá mi. Ó lóun fẹ́ẹ́ gb'owóo irun #India, òun fẹ́ ra aṣo #Egypt fún ọdún. Mo wáá ní, kí ló ṣe irun àti aṣo #Yoruba?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user kosi iro ninu gbogbo ohun ti o wi, awon ni won ko ba wa, sugbon awon olori wa naa ya alajebanu, won o fe daada …
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ope loyeru i eda ba mo iru nro yio dupe ni owo olorun oba modupe temi cc
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Èwo ni ká kọ fún wọn: “Ao pàdé lẹ́sẹ Jesu” TABI “À nsọ̀rọ̀ ìlẹ ibukun na”
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bi awọn kan maa n ṣe niyi ko n ṣe gbogbo igba ni a fẹ gbo itan ta ti gbo ri
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ bá wa kí #GEJ :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú ọjọ́ọ eérú o, ẹ̀yin onígbàgbọ́ òdodo #AshWednesday http://t.co/BtDZtWvBaG
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ese ooo akowe awa omo ajilete ilu ti a te sarin odan ilu awaon omo akin ti ko fara sin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìmàdó ► wild boar ìmàdó jọ ẹlẹ́dẹ̀ inú igbó ńlá sì ni ìmàdó wà wild boar looks like pigs it lives in the wild
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train