text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
láàárín ọjọ́ méje ni a fi ń ṣe ìpalẹ̀mọ́ eré ẹ̀yọ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹkùn jọ àmọ̀tẹ́kùn eranko wo ló jọ ọ̀kẹ́rẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Kọ + orin = kọrin, pa + ẹnu = panu, nu + ìdí = nùdí, ṣu +____ = ṣubú. #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àkóbá ńlá l'èròja kiní ajílẹ̀ tòun apako wọ̀nyí ń ṣe ẹ̀dá ilẹ̀ ayé gbogbo. Àǹfààní ni wọ́n sọ fún wa, ìdàkejì ò sunwọ̀n. #AyajoOjoIle
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lati ìgbayi lọ ní àwọ́n olòwò ẹrú ti ń wọ́ ilẹ àdulawọ̀ lẹyin ní ilú àti àwọ́n ìyokù ní ṣiṣẹ n tẹle
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó ṣẹlẹ̀ ni o kìí ṣe àròkọ rárá! --> http://t.co/M88ugxxf. nkan àràmàndà la mà bápàdé nínú igbó o!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Ewé patanmọ́ dára fún kòkòrò ara. #Patanmo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní àárín àwọn yorùbá ìyẹn ní ayée nàmínnalẹ̀ àwọn ọdẹẹ́ ní agbára tí ó pọ̀ ibi gíga ni wọ́n wà láàárín ètò ìjọba ọdẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
FÍÌMÙ TO GBÁMÚSÉ PẸ̀LÚ ORÍYÍN DIẸ́
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ìdí nìyí tí mo fi béèrè wí pé kí ni orúkọ tí wọ́n ń pè é
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
toò kò jẹ́ bó ti jẹ́ ọjọ́ kan péré ni à ń tọrọ rẹ̀ fún ìṣẹ̀ṣe àbọ̀ ọ̀rọ̀ là ń sọ fọ́mọlúàbí ojúmọ́ ire
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Chaka Zulu mọ̀ pé kò dáa, ìkà l'ó fi ń ṣe. #Nigeria #SouthAfrica #Adulawo #Africa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yoruba dun lede. Eje ka gbe asa ati ede Yoruba laruje. Eku oju mo re, gbogbo omo Yoruba. #TweetInYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ayọ̀ àti àláfíà ni o, ọmọ ìyá mi. ẹ̀yin nkọ́?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó lẹ́wa, ó lẹ́wa, ìbànújẹ́ àti ìṣe kókó.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ti Apa o ba seh shan a Ma ka lori ni #yoruba @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òrìṣà kì í gba méjì lọ́wọ́ ìmẹ́lẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yorùbá ò gbọdọ̀ parun èdè gẹ̀ẹ́sì ò dí èdè yorùbá lọ́wọ́ ẹ kọ́ ọmọ lédè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ejé kágbé èdè wa laruge lóòní..! Ọmọ yorùbá tòótọ́ lemi! B'óbafé mo ìtumọ ohun ti mo n'so, lọ kọ: a b d e ẹ Bó bá mo ìtum…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ajá tó rí ìkokò tí ngbó, Ẹ̀ṣù ò ṣè ìkokò, ajá nii ṣe! :))
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bíi ti àná ifá gba àwọn ọmọ méjèèjì ní mọ̀ran ó ní kí wọn ó ṣe bí ìyá wọn ti ṣe lọ́jọ́ kìnínní àná
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ múra síṣẹ́ o. Pápàpá, wákàtí mélòókan á kọjá, ẹ̀ ó bọ́ sí àsìkò fàájì rẹpẹtẹ o :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Nínú ìka-ọwọ́ wa máràààrún, èwo ni à ń pè ní 'mogajùwọ́nlọ'? #Ibeere #Yoruba https://t.co/QAzJgbEnIV
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn kan wà ní kọ̀rọ̀, tí kò jẹ kí òṣìṣẹ́ àti òṣìṣẹ́ fẹ̀hinti rí ẹ̀tò wọn gbá lásikò. #MayDay #ippis #nigeria
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eni ti ko ba ni'fe iya ti o bi i tokan-tokan, a padanu ibukun nla ni'le aye e @user does making my own Yoruba proverb count? #Naijaproud #wizkid #Nigeria #LoveYourMum #Yoruba #OmoBalogun #Iya #Respect #Love #Africa 💙😍 https://t.co/HQ5HcFwqcW
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Cc @user RT @user: o jeje fun iroko pe ohun ma fun ni omo ti oun ba koko bi ti o ba le fun oun ... http:/ ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bethasda blind sing crew yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojúlówó, ìdánilárayá àti ìmọ̀lára dídára. Mo le fi gbogbo ọjọ́ wò ó. Ó wù mí kí wọ́n gbé e jáde síi ju ẹ̀kan lọ́sè lọ. Yàtọ̀ sí èyíinì, ó kàn sáa dára púpò ni. Òpò nínú àwọn eré olótìtọ́ọ́ jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń kó kí wọ́n tó ṣe é, ṣùgbọ́n, èyí kọ́.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
wahala ni banki guarantee omo yahoo ji owo alaroye gbe si banki won ni nibe lawon onijibiti yahoo yahoo n gbowo pamo si o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìbátan - kindred, relation, family (inú mi dùn, mo rí àwọn ìbátan mi - am happy I see my family) #learnyoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù tó dára. . . . Asetanse lati ipò àṣà ìgbò,o yatọ sí eré tó kù. Mo nifẹ sí wipe awọn ìpìlẹ̀ yàtọ sí òun tí a lérò lati ọwọ fíìmù Afirika, ní ibi tí a tí lè sọ àsọtẹlẹ òun ti o ṣẹlẹ.Genny kú iṣẹ́.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ọmọ Ibo l'ó ju dànsíkí. B'ó ṣe jẹ́ gan-an lo sọ. #SMWLagosTW @user @user https://t.co/wHREEZ2smS
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ ìyá @user, máa 'go on' sọ́'ọ̀ún. #Brooklyn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìyàlẹ́nu. . Bí ìtàn na ti lo lárindin, àwọn òṣèré náà ṣe dára dára àti pé ìparí eré na ò ṣé mo láti ìbèrè. Àwòrán na jágeree. Ìdàgbàsókè tí bá eré noliwudu o
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Mo kí gbogbo òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ẹ rédíò kúu àyájọ́ ọjọ́ rédíò #worldradioday
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ire ni Temi ni gba gbogbo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àkókò ò dúró de ẹnìkan. / Time waits for no one. #yoruba https://t.co/XLOkUKMErW
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Ọbẹ̀ awun l'ó pa awun. #FreeWale https://t.co/9w5yvqTMVl
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
... IWA Ibajee Waa Tiii Dii ASA ... Koo Tii E Sii ITIJU Moo ... #Omo #Yoruba. #OKAY.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí èèyàn bá kú sí inú omi (òkun, ọ̀sà, odò abbl), etí omi ni wọ́n gbọ́dọ̀ sin òkú ẹni náà sìí, Lẹ́hìn tí wọ́n bá ti ṣe àwọn oríṣiríṣi etutu. Ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá ni wípé, ẹni náà ti di òrìṣà omi.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user abi oooo awon ooluko wa o ran asa wa lowo ohun to buru ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kí omùgọ̀ kan máa sọ pé èèbó ló mú afárá wá fún wa o págà kẹ́kẹ́ pa mọ́ ọn lẹ́nu
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O fúyẹ́ o sí pa'ni l'ẹrin. . Ìdíyelé góòlù àwàdà pelu ìtàn tó dára. Lati ọ̀dọ̀ awọn arábìnrin dé orí awọn alátakò,o gbọdọ̀ wò. Ka na so ìdá pìlẹ̀ àlà aìròtẹ́lẹ̀ ati ipá pàtàkì! Mo gba yi. Níye kí ẹ wòó.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ìkìlọ. O ní láti wo ìparí eré yìí nítorí wípé ǹkan ṣẹlẹ̀ ní ìparí eré náà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Mo kí ọmọ lẹ́hìn Krístì gbogbo. Ẹ kú Ọjọ́-Àìkú yìí o. Àìkú tí í ṣe baálẹ̀ ọrọ̀.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo oun tí mó lè sọ ní wípé Eré yìí ni mo dìbò fún ní ọdún yìí
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
29.Bí àjànàkú kò ba gbẹkẹlẹ fùrọ̀, kì í mi odu àgbọn If an elephant is not sure of its anus, it does not swallow whole coconuts. #Yoruba #Proverb #Owe #YorubaProverb #AfricanProverbs
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èyí tó wá burú jù ninu gbogbo rè̩ ni ìtàn; bí ìtàn eré Yorùbá ti ro̩rùn tó, eré yìí kò ní àyínìke Kankan tabi ìfìtànpamó̩, tabi àpe̩re̩ Kankan ó fi o̩gbó̩n àtinúdá hàn.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
oṣù kẹ́jọ ni òjò àrọ̀kúrò òjò arọ̀ṣẹ́yìn ń jẹ́ àmọ́ ó jọ pé kò rí bẹ́ẹ̀ mọ́ òjò oṣù kẹsànán ganan ti ń pọ̀ ju àkọ́rọ̀ lọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kérésìmesì, ọdún olówó, ọdún ọlọ́mọ"""""""" - A kú ìpalẹ̀mọ́ o! :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé bí ẹni ń forin kíkọ ṣe agbe (tọrọ owó) ni ọ̀ràn náà rí, ni a fi pe àwọn òǹkọrin/olórin ni """"""""alágbe""""""""? Àṣàa wọn ni lílọ sóde ijó láti kọrin fún owó. #AyajoOjoOrinAgbaye #WorldMusicDay #Yoruba #Music #orinyoruba #alagbe #learnyoruba https://t.co/82QAxmdYZQ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
in language on law enacting security trust fund igbese lori eto aabo ni ipinle ekiti ati ekun gusu iwooorun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Òwe Yoòbá kan ní """"""""Ọmọ aṣòótọ́ Ìlọ́kọ́ ní í sun ilẹ̀ẹ́lẹ̀, purọ́ purọ́ wọn ní í gorí ẹṣin"""""""". @user #Yorùbá
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jíjí tí mo jí lónìí, mo fọpẹ́ f'Élédùmarè Ọba Alágbára. Ọba pọ̀n mí má jẹ̀ẹ́ n jábọ́. #Ekaaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ááwù. Ó janikulẹ. Igi búburú pẹ̀lú èyí tí ìlú ọba ní èyí
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Sunday Igboho @user, akoni oodua tokantokan #yoruba ronu o Cc @user @user @user @user…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọlọ́mọ tíò ṣẹ̀ tíò mọ̀dí tí òun fi wà lọ́dọ̀ àwọn gbọ́mọgbọ́mọ ẹkún ojoojúmọ́ igbe ìgbàogbo hàá irú ìlú wo nìyìí
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bí èèyàn bá ṣèṣì kọ Ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ ní Burundi, yóó bá ara rẹ̀ lẹ́wọ̀n ni. Burundi: Kọ Ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ —…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó lọ́ra gbígbé àsọtẹ́lẹ̀ Eléèyí fíìmù pàtó jẹ́ ti ní àwọn high junior Circuit.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
mo kí kú oríire o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ègbo èwo nínú oúnjẹ wọ̀nyí ni a fi àgbàdo ṣe ọ̀jọ̀jọ̀ ègbo kàsádà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ipá ọ̀gbíni 7 #BIH yìí pọ̀ #idanoripapa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
5. Oku of Jabata 6. Afonja of Ilorin 7. Toyeje of Ogbomoso 8. Edun of Gbogun 9. Amepo of Abemo 10. Kurumi of Ijaye
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Yoruba Aifarabale. Olori Aarun.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Akowe ko wura☺ aku ojumo oni Oo°˚˚˚°! Ode o dun bi?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Adìyẹ ń jẹ ìfun ara wọn -- https://t.co/MdRwlD0h90
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Sọ àwọn ọ̀rọ̀ ní Yorùbá (pronounce words in Yoruba) Children- àwọn ọmọ Parent- òbí Family- ẹbí Pls subscribe to our YouTu…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: #stateofosun """"omo eni ko le se idi be bere ka gbe f'omo elomiran"""" #osundecides Ife&Ijesaland @user"""" :)
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pẹ̀lú gbogbo kàrámọ̀ ìpani ni ẹ̀ẹ̀rín àti ìṣọwọ́ ṣeré tí ó ń fò sókè sódò láàrín ín pé wọ́n ti tẹșan mọ́ ọ jù àbí pé wọn kò tilẹ̀ ríi ṣe rárá.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bí a bá ń ka #OwoEyo, a óò ní """"""""ẹní, èjì, ẹ̀ta, ..."""""""" #Yoruba #Onka https://t.co/A2i160MGxb
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
... IBON Nii N Sii Eni Paa ... EPE Kii Sii Eni Jaa ... #Yoruba. #OKAY.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Ile eko UNILORIN le awon akeko marun tefetefe fun orisirisi ese http://t.co/ZxpsuEnESB
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀gẹ̀dẹ̀ kò ní gbè odò kó ya àgàn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo ṣọpẹ́ fún Ọlọ́run. Ọba tó fẹ́ mi tó dá mi tó gbà mí là.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwón elétò ìlera fí ókàn aráálu lélẹ̀ lórí àisàn eyi https://t.co/pRAM7pdfOR #Yoruba https://t.co/0RnEmbHann
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Leyin opolopo igbinyanju Per Mertesacker gba boolu alakoko wole fun Egbe agbaboolu Arsenal
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kì í bọ́ lọ́wọ́ èèyàn kó bọ́ sílẹ̀; ọwọ́ ẹlòmíràn ní ń bọ́ sí"""". Translation: """"If opportunity slips out of a person’s hand, it lands in another's"""". Lesson: Don't let opportunities slip off your hand. #opportunity #helpyourself #wisesayings #owe #yorubalessons #yoruba https://t.co/O63HjKJ8yM
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo kí gbogbo mùsùlùmí òdodo ní gbogbo àgbálá aiyé kú ọdún o. #Iléyá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ikú ń kanlẹ̀kùn oúnjẹ àgbáyé àti ewu tí ó rọ̀ mọ́ ọn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òwe yorùbá ní ìròmì ó jó lásán onílù rẹ̀ ń bẹ nísàlẹ̀ odò báwo ni orin sákárà ṣe bẹ̀rẹ̀ ganan ta ló lè sọ ọ́ fún wa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
buhari is juggling no time yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìkòkò dúdú kò yá bù ṣán ọmọ burúkú kò yá lù pa️ ìkòkò dúdú kò yẹ á bù ṣán ọmọ burúkú kò yẹ á lù pa️
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣé ẹ ti ka ewì ọmọge ìwòyí tí mo kọ ►
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user hahaha. Ẹ má fòyà iyá wa. Ati bomi wẹ̀ bí ẹ ti kọ́ wa. A ré èékáná wa. A tún jẹun tó dára lásìkò, a kò sì jẹun jù :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn Ìjẹ̀bú ní bí wọ́n ṣe ń ya èèyàn yàtọ̀ sí ará wọn: """"""""ẹni àkọ́kọ́ tí wọ́n kò mọ̀"""""""" - Lágbájá """"""""ẹni ìkejì tí wọ́n kò mọ̀"""""""" - Tàmẹ̀dù """"""""ẹni ẹ̀kẹ́ta tí wọ́n kò mọ̀"""""""" - Lákáṣègbé. Ní ìgbà míràn, wọ́n ma ń lo gbogbo ẹ̀ pọ̀ nínú gbólóhùn kan náà.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àjọ #NCDC wípé èèyàn tí oonka wọ́n jẹ́ 999 ni wọ́n ní àrun #coronavirus l'ana (22/12/20) ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. |#COVID19 #COVIDSecondWave #COVID19Nigeria #COVID #CovidVaccine #CoronaVirusUpdates #Yoruba #healthcare #Health #wednesdaythought https://t.co/WV6daXyLW9
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Èwo ni ọ̀rọ̀ Olùwà nínúu gbólóhùn wọ̀nyí? A. Òjó pa bàtà bátabàta B. Ògúnjẹ́nbọ́lá dín àkàrà elépo #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù Arie ati Chuko Esiri yénii nípa àfojúsí àtúnṣe sí àwọn ìdíwó tó wà láti ṣe àṣeyọrí.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Yún; meaning ► to go. Yún ► itch, scratch (ara ń yún mi - my body is itching). Yún ►to take-in (Ṣadé ti yún - Ṣadé is pregnant) #InYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user odaa bee aje wipe okookan laa ji ka sunre o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òkòkò ni ẹdìẹ t'ó lọ́mọ lẹ́yìn. Òròmọdìẹ ni ọmọ ẹdìẹ. Kíni àgbébọ̀ ẹdìẹ? #learnYoruba #InYoruba https://t.co/Y3Gg7jojeX
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aku ori ire o ara omo obasanjo adeboye tawon boko haramu yinbon lu ti ya o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Mọ̀jà, mọ̀sá, lakínkanjú fi ńtọ́jọ́ #Yoruba. Decode if you can
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo fi tó wọn létí pé mi ò ní lè wá 🙄 https://t.co/96qNxCW9VC
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo ki @user wipe won ku ojo ibi o opolopo e ni won o se ni oke eepe. Iwaju ni opa ebiti n re si Iwaju ni e o maa lo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilú tí ọmọ ológì ò mọ ẹ̀kọ pọ́n #Nigeria
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
igba iponju laa more to je gidi ko sore mo alabarin lo ku
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fálétí náà ni atọ́kùn ètò àkọ́kọ́ ní yorùbá lórí rédíò àti lórí amóhùn máwòràán fálétí lọ sí yunifásítì dakar ní orílẹ̀ èdè senegal ni tí ó sì gba iwé ẹ̀rí nínú èdè faransé àti ọ̀làjú ní ọdún ó ṣe tán ní yunifásítì ìbàdàn tí ó sì gba ìwé ẹ̀rí nínu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àtìgbà náà lọ ni ó ti di àṣà tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ́ rí ọmọba àrẹ̀mọ ni ipò ọba tọ́sí lẹ́hìntí ọba bá dágbéré fáyé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èèbó Europe ti dé sí wa láàárín. A ti jọ ń ṣe káràkátà, ìṣòwò ń gbòrò. #Nigbatiwonde
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train