text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
...Láì déènà p'ẹnu, Olúwadábírà! Ire oooo... (Translation in the comment below 😁) #yoruba #yorubaculture #yorubaculturalambassador #yorubanimi #yorubanation #urbanyoruba #urbanyorubaman #urbanyorubaboy | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìṣàwárí epo ilẹ̀, bí irinṣẹ́ àti ẹ̀rọ ìgbàlódé ńlá-ńlá tí ń fi epo ṣiṣẹ́ (Industrial Revolution), kò wàhálà bá wa. #IyipadaOjuOjo #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kábíèsí ọba ìyè mojúbà rẹ o mà ṣeun o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré náà lè diẹ láti fi ọkàn báa lọ àmọ́ o to akitiyan tí wọ́n fi síi. Ó dàbí eré Romeo and Juliet ni a ṣẹ ní orílẹ̀-ède Nàìjíríà. Àwọn òbí gẹ́gẹ́ bí àwọn mìíràn fẹ́ oun tó dára fún àwọn ọmọ wọn. Tí o bá fẹ́ràn eré ìfẹ tó sì tún panilérìn-ín, wo eré yìí títí dé òpin, wà á síì gbád... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user America ni àgbà ọ̀jẹ̀ apàlọ́ ti kọ́ọ́ pa àlọ́ fún òyìbó. Ẹ̀yìn tí bàbá padà dé Nigeria ni wọ́n ṣe àkọ́kọ́ ère alálọ̀ọ́ fún ọmọdé. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí ẹ bá ṣàkíyèsí ẹ̀, ẹ̀ ó rí i pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orúkọ ẹranko ní èdè Gẹ̀ẹ́sì kìí ṣe èdè Gẹ̀ẹ́sì rárá. #eranko | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó ní ìtàn kan nípa wèrèpè nínú Ifá. Ó di aago mẹ́fà. #WerepeNinuIfa #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
máa fi omi inú tẹ̀tẹ̀ẹlẹ́ẹ̀gún pa ibi ifo ara máa jẹ ẹ̀fọ tẹ̀tẹ̀ẹlẹ́ẹ̀gún dáadáa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eyin temi e jooo, KINI ALEFI TE ARAAYE LOORUN GAN??? Ruka https://t.co/A5bc0YvNtj #yoruba #yorubalanguage #Nigerian #positivevibes #nigerianblogger #rukasplace @user Dublin, Ireland https://t.co/5HEkSI0Xqd | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ogun ní iṣẹ́ láti dáàbò bo ìlú náà, tí ó wá fi àyè gbà wọ̀ọ́n láti ní ọmọ ogun àdáni wọn. Àwọn ẹrú ọmọ-ogun náà ṣe tán láti jà, n'íwọ̀n ba ìgbà tí wọ́n bá ti fún wọn ní aṣọ, oúnjẹ, ilé tí wọ́n ma gbé àti ohun èlò ogun. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Irú fíìmù u Nollywood yin ni,ìrẹ́jẹ ,Ìtàn atijo ,Ere burúkú | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Báyìí ni yèrèpè ṣe di ewéko tí ń yún 'ni lára, gbogbo igi tí yèrèpé bá dì mọ́n di àwòmọ́jú fún ọmọ aráyé. #WerepeNinuIfa #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ilé + iṣẹ́ = iléeṣẹ́ aya + ọba = ayaba ojú + = ojúgbà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÒWE /PROVERB A ò ní sọ wípé torí Ẹdun jí àgbàdo lóko, kí a gbá etí ìbejì ní ilé, nítorí pé, wọ́n jọ ń jẹ́ Ẹdun. Ẹni tó bá ṣẹ̀ ni kí a báwí. We won't say, because a Colobus monkey stole maize on the farm, and, we slap a twin at home because, they share the same name. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nítorí wípé òní l'ọjọ́ Ajé tó ṣáájú nínú oṣù kẹsàn-án ọdún; Ọ̀wẹwẹ̀ (September), àlàáfíà ara, ọlá ńlá àti ọmọ rere yóò bà s'ọ́dẹ̀dẹ̀ẹ mi láṣẹ Elédùwà. #iwure #OjoAje #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user abi? Hmmmm be ni oooo, tori pe wan fi kowa ni eko nani oo, ko da bi awon omo isin!!!""""ǹkan ti yàtọ̀ #Teachersday | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwa tún rí ọ̀sẹ̀ t'ó bẹ̀rẹ̀ oṣù Ọ̀pẹ lálàáfíà ara. Kíni ó yẹ Olódùmarè bí ò ju ọpẹ! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ire owó ire ọmọ ire àìkú baálẹ̀ ọrọ̀ ire àlà àfíà ire ìfọ̀kànbalẹ̀ ire jaburata ire gọbọi ire kàbìtì ni tia lọ́sẹ̀ yìí o àṣẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A kòì tíì gba òmìnira bí a bá ṣì ń jẹ́ orúkọ kórúkọ tàbí sọ ọmọ wa ní orúkọ ẹrú. Àwọn orúkọ tí kò tọ́ka sí onírúurú èdè abínibí àti ìṣẹ̀lẹ̀ abínibí, àwọn orúkọ tí ó ń mú wa sọ ilé nù. A kòì tíì gba òmìnira rárá bí a kò bá fẹ́ gbọ́ nípa àwọn tí ó ṣẹ̀ wá. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
new abuse alert o n so kátankàtan bii igbakeji oníìjálá | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni tó sùnlọ lábẹ́ igi àgbọn, kó dá olúwarẹ̀ lójú pé fìlà irin ló dé sórí. :) #aworan http://t.co/2U0uPaq9 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Ta ló máa wọlé? #Buhari àbí #Jonathan ?"""""""" <--- Mo reke, mo n Wo! | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi ti isura eni wa, ibe ni Okan eni n wa. Where one's treasure is, there one's mind is! #Yoruba #Proverbs #OmoYoruba #OmoYorubanimi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: """" mo fe alaafia fun venezuela """" Jòwó ..... Jòwó ... Jòwó !!! #ÀlaafiaVenezuela""""èmi náà fẹ́ àlááfíà fún #Nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹni tó ṣìrègún (ṣe ìrègún) ni ẹni tó ṣe oore fúnni nígbàkan ṣùgbọ́n tí kò mẹ́nu kúrò níbẹ̀, tó ntọ́ka sí oore náà ní gbogbo ìgbà | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
toò láti tí ti kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ alákọ̀wé yín a kọjá sí níbití ó ti nlọ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí àbẹ́ẹ̀ rí nkan | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Tí òjò bá dá tán, ti abẹ́ igi kì í dá bọ́rọ́. / When the rain subsides, the (rain water) dripping under trees seldom p… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹnìkínní á kó ẹjọ́ á rò, ẹnìkejì náà á kó ẹjọ́ á rò, ẹ̀yìn ìgbà náà ni àwọn àgbà níkàlẹ̀ yóò tó wí tẹnu wọn. #IdajoNileYoruba #Asa #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ṣé ntorí ìrẹsì tóo gbé fún mi"""""""" hahaha. Ṣàngbà fọ́! Ọlọ́run Ọba ò! :) #erinkeekee | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Omi ò ní gbé wa lọ o. Àmín. » http://t.co/7sQlc9kBYH #WorldWaterDay | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
E dibo! Nje awon Boko Haraamu le dekun ati ma ju bombu kaakiri ile yii ? A. bee ni abi B. bee ko | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo ń gbìyànjú díẹ̀díẹ̀ o jàre | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ejowo kini yoruba n pe ni (1) afurugbin (re mi mi do) (2) komookun (do mi do re)? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré yìí kò dùn rárá, kódà kò ní wu ọmọdé. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Ẹ ṣé ẹ kú àpọ́nlé o :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÀRỌKO / HIEROGLYPHICS If 2 cowries facing each other, is sent to someone, it means, there is an agreement to a decision or course of action Tí wọ́n bá fi ẹyọ owó méjì tí wọ́n kọjú sí ara wọn, ráńṣẹ́ sí èèyàn, ó túnmọ́ sí ìfọwọ́sí ọ̀rọ̀ tàbí ǹkan tí wọ́n fẹ́ ṣe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kò sí orin ìbílẹ̀ tí a ò ní fetí kó ìrírí ayé, àkànlò èdè, ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ àti onírúurú òwe. #Sakara #Yoruba #Ajinde | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Tẹ gàba ✔️ Jẹ gàba ❌ Àwọn Fúlàní ti ń tẹ gàba lórí wa ọjọ́ ti pẹ́, kì í ṣe òní. #Asiko #Asilo #Ede #Yoruba #LearnYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user @user Egberun lona ogoru omo ogun kole bori wahala ile wa– COAS >http://t.co/oXjNdFb9YM | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ah ọlọ́run ọba kówa yọ nínú ìdààmú yìí ẹ kú ìfaradà o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Won Ti Ju Aburada Lu PDP Laya: Etteh Ni Ohun Se Egbe Jonathan Mo.: Olori ile igbimo asoju-sofin nigba kan ri, ... http… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aja kan ki ja omo leyin eku. Wa se iya awon mi kale. Ameen. #happymothersday #culture #Yoruba #ebutecastle @user London Borough of Bromley https://t.co/9enokGfcdm | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
lè bàá jẹ ọba. Lẹ́hìn tí Ọba Àtìbà figile òfin sínsin Àrẹ̀mọ mọ́ ọba, bí Àrẹ̀mọ bá yẹ láti jẹ ọba, Ọ̀yọ́ Mèsì ló ma gbà á wọlé. Bí Baṣọ̀run bá kọ Àrẹ̀mọ láti jẹ ọba, Àrẹ̀mọ ma kúrò ní ìlú, lọ sí abà kan, láti f'ẹ̀yìn tì. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbẹ́sẹ̀ yìí, l'ó mú nǹkan yàtọ̀ gedegbe fún àwọn ìlú wọnnì, kí nìdìí t'ó fi yẹ wọ́n? Wọn ò fi àṣà wọn tàfàlà. #OminiraNigeria #NigeriaAt56 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpinnu Ọdún Tuntun tó o ṣe ní ọjọ́ kìníní 2014, ǹjẹ́ o pámọ́ bí? »» http://t.co/32oVczPP1g #Yobamoodua #Bilingual #Blog #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
nitori owoori awon opc fiya je akano omoose aregbesola tolulope | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kò ṣẹlẹ̀ rí, kò ṣẹlẹ̀ rí, ọjọ́ kan náà ni yó ṣẹlẹ̀. Àìsí ináa mànàmáná fún àìmọye ọjọ́ ni ti wa ń bí. ⚡ https://t.co/EFRnrHU5pg | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀bàyéjẹ́ ni ọ́ ìwọ tí o mú ọmọdé sábẹ́ fi ipá bá ọmọdé sùn | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kọ́nsónáǹtì méjì ò lè tẹ̀lé ara wọn nínú ọ̀rọ̀ àyà fi kọ́nsónáǹtì ń ìdí èyí ni wípé kọ́nsónáǹtì n lè dá dúró ní aiyé tirẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn bíi àpẹẹrẹ ǹkan = ǹ + kan báyọ̀ ń lọ sí òde kọ́nsónáǹtì ò sì lè gbẹ̀hìn ọ̀rọ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user ẹ kú iṣẹ́ ìlú o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user :ko si 'soro,oplolopo jije mimu wa ni repete loni**erin muse | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpèsèe ajílẹ̀, irúgbìn jẹ́ gbígbà lọ́fẹ̀ẹ́ lófò. Èròngbà ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ni kí gbogbo ẹbí nípínlẹ̀ Èkó ó lóko. #IseAgbeNiseIleeWa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tí èyàn bá dúdú riri wọn a máa wípé ó dúdú bíi kóró eso wo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fífì lẹpọ̀n àgbò ń fì lásán, ẹpọ̀n àgbò kìí já #Yoruba #oroyoruba @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ wo #4GB #USB tó jẹ́ pé owó iyebíye àti títóbi gòdògbà ni tẹ́lẹ̀ rí. Ó wá di nkan kékeré tí wọ́n nhá lọ́fẹ̀ẹ́. http://t.co/cW5JKgm8 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Owódayé súnmọ́ ìlú Nubia, Tigre àti Axum, pẹ̀lú Punt. #Irinajo #Ijebu | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òní ni Àyájọ́ Ọjọ́ Ìtumọ̀ Àgbáyé. Gbogbo wa ní @user àti ẹ̀ka rẹ̀, @user ń kí àwọn tí ó ń tú ìmọ̀ ìròyìn àgbáyé sí onírúurú èdè abínibí kú iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ń ṣe. 💚 #ITD #ITD2019 #WeAreIndigenous #Language https://t.co/1R6HvvQuM9 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹni ọ̀rẹ́ dà kó má ṣe bínú ẹni abínibí ńdani those betrayed by friends shouldnt be offended even siblings betr | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀bu burúkú !. . Èyí ni Eré oníṣe burúkú tí mo ti rírí ní Ilé ayé mi! | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Máṣe tẹ́tísí èsì òdì yìí. . . . Mo ti wòye àwọn kan kò le mú òótọ́ mú kí wọ́n parọ́ irọ́ ni fíìmù ńlá kìí ṣe òótọ́ oun gbogbo nínú fíìmù ṣùgbọ́n Adéwálé ti sọ béè sùgbọ́n awo Tilbury àtijó jowú lásán.... Mú fíìmù fún oun tí ó jẹ́ kí ó sì yé ayé jẹ́ bu... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Ó ní """"""""kí èṣù gbà, kẹ́bọ ó dà fẹ́lẹ́bọ, a dífá fún òyìnbó ọmọ a tukọ̀-lọ́kọ̀, ọmọ a gbẹ́ rebete lóríi rekete ... #Orunmila #… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àtàrí/ìpọ̀nrí/orí - head (Àdìsá ju òkò lu ẹyẹ látàrí - Àdìsá threw stone at the bird's head) #InYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí la npè ní àtànpàkò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
16. Yàtọ̀ sí ọ̀pẹ̀lẹ̀, èwo ni a tún lè fi wo ìṣẹ̀dà? A) Ẹẹ́rìndínlógún B) Obì dídà D) Iyanrìn-títẹ̀ Ẹ) Agbigba F) Ọwọ́ wíwò G) Omi wíwò #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo yára wẹ́ ata rodo díẹ̀ lórí ọlọ ẹ̀wà wooro bí i ẹ̀wà ìbejì ni mo sè ìṣasùn lásán ni mo kọ́kọ́ gbé sórí àrò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀rọ̀ rè é o ọ̀rọ̀ rè é o ọ̀rọ̀ rè é o rẹpẹtẹ ṣe bí ẹ mọ íngílíìṣì íkà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìṣe burúkú | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Fíìmù nla. . . . Mo ṣiṣ̣ẹ́ lóri fíìmù yìí. Mi ò kìí sába wo àwọn eré tí mo bá ti ṣiṣẹ́ lórí won-on rí, ṣùgbón èyí yanílẹ́nu. Ade John kúusé. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ẹ bá wa ké músò! Ohùn Àgbáyé ní Èdèe Yorùbá pé ọdún kan lórí gbàgede Iké-ẹyẹ. @user @user Ẹ bá wa ṣe nínú iṣẹ́ ìlú, ẹ darapọ̀ mọ́ wa!!! #MyTwitterAnniversary https://t.co/1KYvqAfRDj | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a mọ̀ wípé olódùmarè ni ọba aláṣẹ lọ́run àti láyé àṣẹ rẹ̀ ni ohun gbogbo fi ń bẹ bí ẹ̀bẹ tí ohun gbogbo fi wà bí ẹ̀wà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
8. #PariOweYii ní ọ̀nà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: òjò tó rọ̀... #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òyà = comb. Óyá = get set. Ọya = Sango's wife. Ọ̀yà = hedge hog. #InYoruba #learnyoruba #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kíni ìdí tí a fi gbọ́dọ̀ ṣ'òfíntótó láti mọ irú ìdílé tí àfẹ́sánà ọmọ ẹni ti wá nínú àṣà ìgbéyàwò? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré tó mórí wú , tó sì mórí yá , àti pé o fi hàn gedengbe pe Ìtàn ìrírí ayé ni. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
aanuoluwapo gods mercy is great aarin refers to centremiddle aarinade in the centre of the crown aarinola d centre of wealth | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A kì í fi ọjọ́ kan bọ́ ọmọ tó rù. / A lean child can't be fattened in one day. [Good things take time; be patient] #yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#np Ise Agbe Titled:Ogbin Akuro https://t.co/5MWSdAg85K #yoruba #SaturdayThoughts #agriculture https://t.co/xvsYynQ8y9 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ijoba ke ni ilu naija ni bo le ti fe ri ina loju popo nigbati awon eniyan o ni ina lati sun ni ile won | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user Mo ṣe tán àti gbé gbètugbètu tí mo jogún bá jáde nítorí àwọn """"""""olórí ibú"""""""" wọ̀nyí. À ní ataare ló jẹ́ mí, ohùn wà. 😡 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ní orílẹ̀-èdè Turkey, ẹgbẹẹgbẹ̀rún méjì àbọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ni wọ́n jókòó ṣe ìdánwò ìgbaniwọlẹ́ sí Ifásitì. https://t.co/j6… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọ́n á ní ojú ti ajọ̀sán ta ni mọ ìdí tí wọ́n fi wí bẹ́ẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ jẹ́ ń sọ pé àwọn arab larubawa ló pe ilẹ̀ adú ní sudan | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
e ku igbadun e si ku dede iwoyi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Iléṣẹ ẹlẹ́rọ ìbánisọ̀rọ̀ #MTN #AIRTEL #ETISALAT #VISAPHONE #GLOBACOM ẹ wá wọ̀rọ̀kọ̀ fi ṣàdá, ẹ wá nńkan ṣé sí sége-sège iṣẹ yín o #WTISD | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ikú àgbágbìí tún ti mú ọ̀kan lára àwọn àwòrò ṣàṣà eré ìtàgé ilẹ̀ Yorùbá lọ ọ̀run àrèmabọ̀. Bàbá Jímọ̀ Àlíù tí gbogbo ènìyàn… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojúlówó ere tí kò dára rárá nìyí. . . . . Ìtàn yìí ní àbùdá tó dára. . . Lóòótọ́ mo fẹ́ràn ere yìí, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ó olólùfẹ́ sinimá ilẹ̀ òkèèrè, ère yìí dàbí èyí tí a dàkọ. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ẹ sọ fún aláṣọ ìgbàlódé kó'rọra, kó'ṣe jẹ́jẹ́. Ákísà ti lọ gbári!!! /// Tell (warn) a modern dresser/fashion enthusiast to be mindful/careful, to step with caution... Because lots of have turn to rags (gone with time) #Yoruba #Proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òun tí mo wó kò wù mí | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
oro apoda ni un so igba ti fi enu warofu nibo lo wa lo ka ofin cybercrimes prohibition prevention etc act | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user #Edumare a je ko sese o. #Ire o ::)"""" Àṣẹ o!!! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí wọ́n ṣe ṣe fún ọba Akítóyè Èkó 1845, Prempeh1 ti #Ashante 1896, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe fún ọba Ovonramwen #Benin 1897. #Amunisin | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ó hun ti onikaluku n lo aago fun yato sirawon, elomiran a maa loo fun oge şişe yato si fun ondiwon akoko. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
...beesini won ni anfani láti fi e si àpámó lai kókó fun e ni anfani láti ba àmòfin re sorò , #Law2go #HuamnRightsinNigeria #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Squirrel ni lédè Gẹ̀ẹ́sì, àmọ́ ikún àti ọ̀kẹ́rẹ́ làwa ń pè é. Ikún ni ti orí ilẹ̀, orí igi lọ̀kẹ́rẹ́ ń gbé. #learnyoruba #language #InYoruba https://t.co/L6BPUzgo9T | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwon obinrin ti ìbàrà ìdí won tóbi a maa je oní ilera tó pé beeni won a maa ni laakaye. #TweetinYoruba @user @user @user https://t.co/g8CPkErs1j | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ni ile aye ti wọn ti n fojú fẹ́ni ti wọn kii fi ọkàn fẹ́nitani oluwa rẹ̀ fẹ́ yìnbọn si | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Njẹ́ ẹ mọ̀ pé tako tabo ní ńwọ agbádá láyé àtijọ́? #orisa #Osun #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó bíni nínú òsì rínilára. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
èmi kì í ṣahun rárá lọ́wọ́ kan ni mo ti tẹ̀lé yín padà a ò kúkú kó followers wá látọ̀run️ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ aṣòótọ́ Ìlọkọ ni í sun ilẹ̀ẹ́lẹ̀, purọ́ purọ́ wọn ni í gorí ẹṣin. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.