text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
@user Fariga: Agbenuso fun Aare Jonathan. Dokita Reuben Abati so wipe Itara lo hun damu awon ti o hun un pe Aare Nijeria Ebele ni Omugo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìlú ẹgbàágbèje oníṣọ̀nà. Ìlú tí wọ́n ti ń gun kẹ̀kẹ́ kí wọ́n to gun ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́. #Amsterdam | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ija ti feju bayii o! Sanusi Lamido fee koba Jonathan patapata- Alaroye | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré àgbéléwò yìí nílò ìyìn tó ju eléyìí lọ torípé ó jẹ́ eré ṣìṣe tí akójọpọ̀ àwọn ìsẹ̀lẹ̀ rẹ̀ kún ojú òsùwọ̀n. Mi ò tíì rí eré àgbéléwò nípa àjàkálẹ̀ àrùn bayii ri, eléyìí jẹ́ titun. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Gbogbo imalẹ̀, alálẹ̀ ilẹ̀ yìí títí kan bàbáà mi lálákejì ìbà ni mo ṣe o, kí n tó túṣọ lójú ìtàn eégún. K'ó jú mi í ṣe o #Eegun #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Suaib sábà ma ń kó èèyàn jọ lóòrèkóòrè, yó ka ki ní kan sí etí ìgbọ́ wọn, pàbo lèyí jásí, kò sí ẹní gba ẹ̀sìn rẹ̀ gbọ́. #IslamNileYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ààrẹ buhari sọ̀rọ̀ nàá nígbà tó n sọrọ níbi ìpàdé commonwealth ní westminster lọjọru ọsẹ ṣé lóòótọ́ ní àwọn ọdọ́ nàìjíríà kò fẹ ǹkan ṣe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èmi Ajírọtútù lágbẹ̀dẹ, alọ́nà àrà, kì í tán nínú igbá osùn! """"""""♪ Èmi náà kọ́ o lọ́run Ọbaaa mà nii! ♪ ♫"""""""" *ohùn #sirshinapeters | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user tani e n tan pelu esa yii laaro kutukutu. Enu yin dun | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Agbara miiran ti o dara ti bajẹ nipasẹ kikọ buburu. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Bó yá lẹ mọ̀ pé Jesu nìkan kọ́ ló wọ ọ̀run lọ lẹ́yìn t'ó jínde? #OjoOse #IsinmiOpe #Yoruba #Ifa #Easter | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ojú àwọn adigunjalè tó kó ẹrù benin ní rè é pẹ̀lú ẹrù olè tí wọ́n jí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí òkété bá dàgbà, ọmú ọmọ rẹ̀ ní í mu. A ò ní ṣán'kú lójú ẹ̀mí òbí wa o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èdùmàrè jọ̀wọ́ jẹ́ ká la ọdún yìí já ẹ kú àmójúbà oṣù ọ̀pẹ o ẹnu ọpẹ́ẹ wa ò ní kan o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àyálò èdè ni àlàáfíà, pọtimọ́tò, àǹkóò, ìrẹsì, èwo tún ni ọ̀rọ̀ àyálò nínú ìwọ̀nyí? A) fàbú B) Ẹ̀gi D) kòkó #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Amin Ase Eledumare!!! """"""""@user: Ẹ ká alẹ́ o. A ò ní ráburú lọ́dún tuntun o."""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oro Ajimobi ni'a mu wa si Iranti yin: """"""""Ajimobi ti ba Ibadan ję o Ole ni yin boda Isiaka, ę ta ile we"""""""" #TweetinYoruba h… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí, wò ibi rere gbé mi dé, ẹsẹ̀ wo ibi ire sìn mí yà. Nítorí orí ni ẹjá fi ń la ibú jà, nítorí orí ni àkèré fi ń wẹ̀ ni odò. Oríì mi, àpésìn! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Se o ti so fun ogbeni Wenger pe o ni le gba boolu ni Ojo aiku? #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Aka ni. Yooba a ni: """"""""""""""""o tiju ju aka lo"""""""""""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fẹ́ràn ọmọ làkejì rẹ bí o ṣe fẹ́ iraà rẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
á di owó owó á máa wọlé kí lẹ tún ń dúró dé kíá ká máa gbọn jó ojú ẹ̀ àbí básí bí èdè ẹ̀gbá ìyáami | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Sísìn ẹlẹ́kejì ejò ó!. . Mo wo “Fifty Series “ mo tún wo Castle & Castle torí ojú Tola faramí. Mo féràn eré oní pele sí ipele yìí, ma sí ní ìfé pé kí sísìn kejì jáde. Mí ò féràn pé ẹ́písòdù tó kù ló kù mí kù. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ fúnmi ni sísìn ẹlẹ́kejì oo!! | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
#LayajoOjoOni ni odun 1854 ni awon omo egbe Oselu WHIG ko ara won jo lati da egbe oselu Republican sile ni Ilu Wisconsin ni ile Amerika | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ̀mí ọmọ ènìyàn ò já sí nkankan ní Naija o :( | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#YORUBA Iforowanilenuwo 🗣️. Awon ara Biafura fe ki Nijeria o pinya. Ki ni awon omo Kaaro oji re fe fun ile Oduduwa. Dibo👇👇 #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: E lo #TweetYoruba tabi #Yoruba so gbogbo tuweeti yin oooo https://t.co/lwCuThtgot | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ki la ma wa ri se oro awon daran daran yi bayi? Wan ran eni eleni lo si orun alakeji https://t.co/oEXBcrjpcI | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Njẹ́ mo kí gbogbo ẹ̀yin olórí ire bí? Mo kí apọ́nbéporẹ́, mo kí dúdúriri. Mo kí òmìrán mo kí ìkérégbè. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
* 40 jẹ́ ogún méjì 20 x2). Ìsúnkì wá fún wa ní OGÓJÌ (40). * 180 - ogún mẹ́sàán (20 x 9) = ỌGỌ́SÀÁN * Àádọ́ jẹ́ ẹyọ òǹkà gangan, tí a yọ mẹ́wàá kúrò nínú rẹ̀. B.A 60-10=50 (àádọ́ta). Èyí lọ títí ó fi dé 170 (Àádọ́sàn). | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aiyé nlọ a ntọ̀ọ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: A kìí wo ago aláago ṣiṣẹ́. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ ẹ ò rò wípé àtúnkọ rẹ̀ láti gẹ̀ẹ́sì sí yorùbá kò ṣe ìdàgbàsókè fún èdè yorùbá àti ìdàgbàsókè èdè náà dont you think a rewrite of it from english to yorùbá doesnt help the growth of yorùbá language the name could reflect its function | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù gidi àti ìsesí àwọn òșèré tí ó máyàn lórí.. . Ojúlówó ìtàn gidi, ìṣọwọ́ ṣeré gidi àti ì dá ẹ̀rín pá òșónú rere ni wọ́n pò pọ̀ sí ojú kan. Fíìmù tí ó mú ara gbá yágíyágí àti àwọn òșèré tí ó lé kenkà. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
se oro nigeria oni wa su un ati bayi bi eniyan kan ba yaso paaaaa ni nigeria ati oga ati bere si ni kigbe un us se wan fi ayi lojuti se wa ni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé àti ìkókóbìnrin àti ìkókókùnrin ni a máa ń lu etí fún láyé àtijọ́? Àwọn Yoòbá ka èyí sí àpẹẹrẹ pé ọmọ náà yóò máa gbọ́ràn. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
whala ti yin ni yen egbon awa o ni gba ki ta wa lopo nkan ti o ba ma gba la ma fun edake shobolashan | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Se mo le ba e soro ninu apo ikoko elemi renikan lori twitter #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nígbàtí ìyáa Ríyìíkẹ́ bíi léèrè pé 'ẹja n bákàn', tí Ríyìíkẹ́ sì ní """"""""ẹja ni o""""""""... #Ejanbakan #idahun #Yorùbá #AkanloEde | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ajé Olókùn. Ajé Onírè. Ajé Ṣálúgà. Gbé ire owó tútù tí ń d'óṣì-pa-àgbàànà kò mí. Bùn mí níre owó tabua, nítorí owó ló dùn ún jayé, láìsí owó, kò sí ènìyàn. #iwure #OjoAje #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀la ọjọ́ọ̀ míì ọjọ́ọ̀ ire ọ̀kọ̀ọ̀kan la ó jìí oooo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí a bá ní pé @user 'dára bíi egbin', kí là ń sọ? Kí ni egbin? #ibeere #YorubaQnA | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Iwo omo yi 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮 Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #owambe #yoruba #oodua #oduduwa #ondo #oyo… https://t.co/jjs2ON1wQw | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ ìwọ mọ̀ wípé awuyewuye àròyé ọ̀tẹ̀ bẹ́ sílẹ̀ nígbà tí a pa ajamï àdàlù èdè lárúbáwá tì tí a bẹ̀rẹ̀ sí í kọ èdè yorù | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá rí òṣùmàrè lókè ẹ ṣèrántí pé Ọlọ́run ò ní payé run pẹ̀lú òjò mọ́. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àgbọn l'ó ní kí n gbọ́n Ọlọ́gbọ́n púpọ̀ ṣá l'agbọ̀n í ṣe Gbogbo ènìyàn tí ó ṣe ìlérí fún mi tí ó ti fi tì, nítorí wí pé òní ni ọjọ́ Ẹtì tí ó kẹ́yìn oṣù Ògún, kí Lákáayé ó mú kí ọkàn rẹ̀ ó là gààrà, kí ó sọ nínú onítọ̀hún kí ó mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ fún mi. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
À ń kì í à ń sà á, ó ní òun kò mọ ẹni tí ó kú. @user A ò ríná lò dà bí alárà, ìyẹn ò sì ní kí ẹ máà mú ìwé owó iná níparí oṣù. 👎 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Èrín àrin t'àkìtì... òrò burúkú t'òun t'èrín...Jonathan gba sátidé lówó re ó gbé sunday le lówó | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oṣù yìí náà ni í títí ọ̀ṣẹ̀ kéjì lágbára ọba alèwílèṣe ire o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àláfíà ni o. Gbogbo wa ń ṣara ridin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Masanfani eda ni arakunrin Jose mourinho. Eri WA pe ako fun ni ikola Enu Rara Pelu Awon oro alufansa t'on jade loore koore. #TweetInYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Abe """"""""@user: Ó dáa. Kí ló kan ọba ní ìkó?"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oníṣègùn lórí pẹpẹ ní | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kárími. Àti ariwo. Àpọ̀jù Òdo ǹkan náà. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
opo la pe di e lao fi fun ni oro messi ooo rt ẹ̀dá ọmọ ènìyàn ni ọ̀gbẹ́ni messi yí àb | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user @user @user @user @user @user Kí nìyẹn fi kàn wá? Kò bá à ru igi, k'ó rù ju èyí tó ju igi lọ fi rán ara rẹ̀ ńlé ìwé, ṣebí alátiṣe ló máa ń mọ àtiṣe ara rẹ̀. Ojú àánú ni @user ń wá, ojú àánú sì ti fọ́, ti ìkà l'ó kù. Bàtà ni @user ò rí wọ̀ lọ sí ilé ìwé ni tìrẹ. Igi ṣíṣẹ́tà ni báyìí 😒 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iléésẹ́ radio nigeria sèlérí ìdàgbàsókè bá àwùjọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ewe osepotu rt ní ayéàtijọ́ kíni wọ́n máa ń lò fún ẹ̀fọ́rí tàbí araríro nílẹ̀ yorùbá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ ṣé járe, ẹ bá wa bèèrè #20billion owóo wa """"""""@user: #WhereIsOurMoney?! (@user NNPC Building) http://t.co/sdZdVrLkOV"""""""" #WeWantTheTruth | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nítòótọ́, àwọn ọ̀nà ìtọ́wò díẹ̀ sìi àti iṣẹ́ ọ̀nà láti gbe àwọn ọjà sínú fíìmù kan, láìsí nítòótọ́ bórí àwọn alábara. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ó mú mi wà láyé, o ṣeun o. Ó mú mi wà láàyè, o ṣeun o... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Ta ló ma à ṣoríre?"""""""" Èmi ni ma à ṣoríre | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
̣Provérbio Yorùbá *Iná l'ọmọ aráyé le pa; Kò S'ẹni tó lè pa èéfín* """""""" humanos só podem apagar o fogo, ninguém pode apagar a fumaça """""""" #cultura #candomblé #yoruba https://t.co/cRpvi8HLPL | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọjọ́ wo la mú Ṣẹrẹ náà, tí oṣù Ọ̀wẹwẹ̀ tún ti f'ìdí rẹ'mi! Oṣù tuntun ti lé ténté. Àsìkò ò dúró dé ẹnìkan. 2016 kú oṣù mẹ́ta. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aàfin Ọ̀yọ́ rè é ní òde ònìí. Ọdún tó kọjá (2013) ni mo ya àwòrán yìí #Oyo #Aafin #Palace http://t.co/dJzHcHNA7J | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oore yèyé ò oore yèyé ọ̀ṣun gt | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Amin. Ati emi naa l'oruko Jesu Kiristi """"""""@user: Ire mi kò ní rékọjá mi o. Ẹ̀yin nkọ́?"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọbabìrin ìlú gẹ̀ẹ́sì mà kú àyájọ́ ọgọ́ta ọdún tó ti gorí oyè o kádé pẹ́ lórí ki bàtà pẹ́ lẹ́sẹ̀ o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀yin ìyáa wa, ẹ dẹ́kun àṣàa à ń fi owó sínúu brècíà, ẹlẹ́ran alápatà, ẹlẹ́ja, elépo àti gbogboo wa kan ọlọ́pàá, agbèrò ojúu títì. #Naira | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lójijì ni ìyá ẹkùn já ara rẹ̀ gbà lọ́wọ́ #Attah, ó sá lọ sí agbègbè kan ó gbé ara rẹ̀ sánlẹ̀, ẹ̀mí bọ́. #ItanObaIgala #Yoruba #Iddah #Kogi | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yorùbá ti wọ́pọ̀ gidi lórí twitter báyìí o á wúmi pé lọ́jọ́ iwájú kó tún gbòòrò síi dáa dáa ṣé ẹ ti tẹ̀lé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user 🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇳🇬 Yiye ni ye eyele. ibi gbogbo ni ro adaba lorun. ara a tu yin o, okan yin a bale o, ema doju ti Nijeria o! @user #Nigeriavsiceland https://t.co/Pcd14GCS8J | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wahala eto idibo alaga ibile! APC Kwara jawo ninu ejo ti won pe tako PDP | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Abike aya rere: Igi leyin ogba Obesere https://t.co/kLis4zRRlY #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fọ́nrán àwọn tó mú igbega bá àṣà àti ìṣe yoruba lọ́nà iwuri ologbe olóyè hubert adedeji ogunde ️️ a bíi si ipinle ogun nigeria ni odun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user pelu emu ogidi lati inu igba. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user ti tan ni Kwara Oju ti la Oto ge https://t.co/8ruDrUcv01 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwàdà àti ìgbádún. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
alaye delade ti aposteli adekayode salako fun osu keji ti oṣu karun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Nje e ti gbo? ...pe apa kokanla YEEPA ti di bale gude lori http://t.co/XSaBfpdOib @user @user @user @user… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Àṣìwí ò tó àṣìsọ. Ìyá ọba kan wà láyé àtijọ́ tó pe'ra rẹ̀ ní Ìyá ọ̀bọ. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àsìkò á ṣe dédé láti ṣe ohun tó tọ́. #MLKDAY | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a bí wa nílé ẹran a sì ń hùwà àgùntàn ṣé nítorí olùbọ̀bọ̀tiribọ̀ yìí náà ṣá ṣíọ̀ kẹ̀lẹ̀bẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: E ku ogbon! Amoran wo ni e ni fun bi a ti le maa se bii ara wa tooto? https://t.co/1ooJjjvu0M | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: E to ore yin kan lo ti o je elesin Musulumi ke. RT @user: Níbo ni olúwarẹ̀ ti lé wá rí ẹran iléyá jẹ báyìí o? :) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ àdúrà ti bẹ̀rẹ̀ wọ́n ní àdúrà tí ọmọ nàìjíríà gbà lọ́jọ́ ẹtì tó kọjá ló mú yege bó bá jẹ́ òótọ́ kí àwọn aládùúrà ìjẹ́rin ó tún ṣe bẹ́ẹ̀ kí a borí argentina láṣàálẹ́ yìí àbí báwo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mi ò ti wo fíìmù Nollywood ríi , tó fi jẹ́ pé ìgbà àkókó ti ma wò ó , ìwárìrì nípaeré àgbéléwò láti ọwó oolùdarí Biyi Bandele tí ń jẹ́ “Fifty" mú mi káká. Nígbà ti mo wò ó dópin , ko féré yàtò si eré àgbéléwò ti ń je “Dynasty" tí a wá ṣe ni ìṣe ti àwọn adúláwò. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
welcome to the th month oṣù agẹmọ or oṣù kéje or oṣù efà ọdún here is my message to you in this month of care ire o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Mo ti fẹ́ sọ wípé ẹ gba PHD nínúu Jíjí Túwíìtì Onítúwíìtì, ṣùgbọ́n mo gbé e mì, n kò sọ bẹ́ẹ̀ mọ́. Bí ẹ bá fẹ́ràn-an ìṣàmúlòo @user púpọ̀ lóòótọ́ bí ẹ ti ṣe wí, ó yẹ kí ẹ gbóríyìn fún òǹnitúwíìtì, tàbí kí ẹ ṣíra tẹ """"""""""""""""retweet"""""""""""""""" 🔄 tàbí """"""""""""""""like"""""""""""""""" 👍🏿 ni. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mi o fe ki ajo LASTMA ati VIO ni awon araalu Eko lara"""" Ambode@user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Dídùn dídùn là á sọ̀rọ̀ oyin Dídùn là á sọ̀rọ̀ iyọ̀ Dídùn ni kí ayé máa sọ̀rọ̀ mi Eré là á fi ọmọ ayò ṣe... #Ife #Yoruba #Ifa #EjiOgbe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ara tu ni, àfí bi ìgbà tí eéwo ẹni bá tú :) #yoruba#LagosState#Osun#Ogun... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ago should be coffin then, poosi """""""" @user: @user, """"""""òkú ò mọ̀ iye tí à ń ra agọ̀"""""""". Kí ni agọ̀? #Ibeere #Yorùbá"""""""""""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Rọra ṣe o, rọra ṣe. Ọmọ ẹ̀mí rọra ma ṣe ... """" @user gbe orin tuntun - Iṣẹ́ Òru #Vigil jáde http://t.co/NkfJ5xjfzg"""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a father is a banker provided by nature ~ baba jẹ alakoso ti a pese nipa iseda ~ tunjiofr | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user kódà kò pẹ́ mọ́, àwọn irúnmọlẹ̀ ti sọ bẹ́ẹ̀, ààkà ti tú sépo @user| @user @user #OtitoLoMaLekeOmojuwaAtiAdeyanju | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òwò báwo? Ẹ tún gbìyànjú sí i https://t.co/khm5K2Mxx6 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nítorí wípé, wọ́n gbàgbọ́ pé, àwọn àbíkú ọmọ kan náà ma ń padà sí ọ̀dọ̀ òbí kan náà, wọn ma fi àmì sí ara òkú ọmọ náà. Bí àmì náà bá wà lára ọmọ tí wọ́n bá tún bí, wọ́n ma tètè mọ̀ wípé, ÀBÍKÚ ọmọ tó lọ ní ọjọ́ sí, ló tún padà wàá. Àwọn Yorùbá gbàgbó wípé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lọ́tìtọ́ọ́, ọ̀rọ̀ inú eré ìfẹ́ tí ó ṣe é fojú tẹ́ńbẹ́lú jù tí mo ti wò rèé. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: A n jade lo ni eni Eledumare,owun tao je lan wa lo baba ki ama pade owun tio je wa,ijade wa loni ki ama pade agbako @user ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.