text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
RT @user: Hmm! Afi ki Eledua maa fi iso e so wa""""""""@user: Ọdún ń yí lọ biribiri.""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user B'emi se ri o; t'a ba mu iwa pele, oyaya, iteriba, ife omol'akeji, akin ati isotito, kitun l'oku lati je om…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olúwa jí wa 're
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Freaky ladies, ejo, Ibo le wa... mo fe ba gbogbo yin soro 😂😂😂😂😂 #Yoruba😈 https://t.co/aSNwIFPrMi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ẹ ǹ lẹ́ mọ̀ o. Ẹ kú iṣẹ́ náà, níṣe ni mo mọ ń fẹ́ràn-an yín ń'nú eré :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
In Yorùbá ìgbìmọ̀ means committee #Yoruba #yorubaword http://t.co/KUKEfFAXo5
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ ṣé màámi ẹ̀bẹ̀ ni mo bẹ̀ elédùà dákun lọ́ra ẹ̀mí ìyá mi kí wón ba jẹun ọmọ pẹ́
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ wí fún ẹni tó ń fi ọlọ ata wé èyíkéyìí ẹ̀rọ ìlọta òní pè kò m'Ẹ̀yọ̀. Ẹ bíi bóyá ó ti jẹ ata tí a lọ lórí ọlọ rí? #Iseselagba #emafiwe https://t.co/ApbtVE0yZP
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ti won ba n gunyan ninu ewe ti won rofo ninu eepo epa emi ayodele omo olofintuade ng o yo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Beeni. Itan fi ye wa wipe Arabinrin Flora Shaw to je iyawo (tabi orebinrin) Lord Lugard ni o so oruko yii. @user @user…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìyá bàbá òbí alágbàtọ́ iléìwé ẹ fèdèe yorùbá kọ́ àwọn èwe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oní-nǹkan lè wò ṣùṣù, kó pa ẹran ọ̀sìn bẹ́ẹ̀ lára nípa sísọ ọ́ di aláàbọ̀ ara, kò sófin tí yóò mú u fún ìgbẹ́sẹ̀ẹ rẹ̀. #IdajoNileYoruba #Asa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọjọ́ kan pẹ̀lú o. Ẹ kú ìgbáládùn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojúlówó!!!. . Eré yii ní ìrírí ayé nínú ní àwọn apá kan!. . Àwọn èèyàn máa ń yá aṣọ ati ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ láti bù ga, wón a pa irọ̀ lójú méjèèjì láti le sọ wípé wọn jẹ́ nkan. Àwọn ènìyàn máa ń fi àṣìṣe wọn kẹ́kọ̀ọ́, wọn yóò sì ràn wọ́n lówó.. . . . Eré á panilérìn pẹ̀lú àwọn àwọn ẹ̀kọ́ tó dára bi pe gbogbo oun tó ń dán ...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
6. Èwo ni ọ̀rọ̀ Olùwà nínúu gbólóhùn wọ̀nyí? A. Òjó pa bàtà bátabàta B. Ògúnjẹ́nbọ́lá dín àkàrà elépo #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ta lo buru ju laarin Sango ati Ogun? (Audio) #Ogun #sango #yoruba https://t.co/8RcJG7dim3 https://t.co/H8pATm8Zmq
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Àjekún ìyà ni ó ję. Ęni tí ò tó nií nà tí ó dè nà deni, Àjekún ìyà ni ó ję! #TweetinYoruba #TweetInYorubaDay
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bẹ́ẹ̀ni oooo alágbẹ̀dẹ̀ ìrèmògún ọmọ àwíṣẹ̀ afojoojúmọ́ ṣọwọ́ owú gbẹ̀dẹ nílé arọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aisi nibe ni aiba won dasi oruko mi oluwafemi adebodun ilu eko ni mushin ni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ o mọ èrèdíi rẹ̀ tí a fi máa ń wí nípe """"""""ó fi owó jó Gẹ̀lẹ̀dẹ́?"""""""", ìpàdé di ọjọ́ Ọjọ́rú tó ń bọ̀, 8/3/17, láago kan ọ̀sán. #Asa #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orí ni alákàn fi ń ṣọ́rí, iṣẹ́ kékeré kọ́ ni kí ọmọ aráyé ṣèfẹ́ ẹni. Ó ní bí Ọ̀rúnmìlà ṣe kọ́ wa, kí ọmọ aráyé ó ba fẹ́ 'ni. #Ife
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀yọ̀ o ayéelé ẹ yọ̀ o ẹ̀yọ̀ baba ntàwa tó ńfi góòlù íṣeré àwa ò lè sanwó olúbodè ó dilé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Dearth of regard that emboldens a peasant to come to town semi-clad."""" """"Àìfinipeni, àìfèèyànpèèyàn tíí m'árá oko sán bàǹtẹ́ wọ̀'lú."""" #yoruba #yorùbá #english #language #aáyanògbufọ̀ #translation #dm7 #dm7th… https://t.co/cGgxqww4ly
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eni ti wan ba fe sunje okin fi epo pa ara ogbon ayinike lati da oju ijoba ati ru o bu ewa rara je je
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orúkọ òmíràn fún ẹ̀dá èèyàn ní yorùbá ni ọmọ adáríhurun ẹ̀dá tí ó dá hu irun ní orí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ikú omi ní í pa ọ̀mọ̀wẹ̀ nǹkan tá a mọ̀ ọ́ jẹ ní í pa wá ni ò jẹ́ kí ẹ̀mí wa ó gùn ní í gé ẹ̀mí wa kúrú bí wọ́n ṣe ń gé
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nínú ìwé eré oníṣe yìí wọ́n wí fún adéagbo títí kò gbọ́ wọ́n sìpẹ̀ fun kò gbà nípa àwọn ìwà ìbàjẹ́ tí ó ń wù àfi ìgbà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹn mo wá fàṣẹ olódùmarè bọnu ǹjẹ́ gbogbo ibi ọ̀nà ẹ bìlà ẹ paradà di ire torí ọmọ ọlọ́nà fẹ́ẹ́ kọjá ẹ̀là
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ti e ba ni eniyan ni'badan,won le lo si Lawal and sons ni Alekuso,o daju won o ri nibe.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sorosoro nimidakun ma je ki n fenu koto ri enu orofo lo n porofokenu temi ma se pami
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
7. #Parioweyii Gbajúmọ̀ ju owó lọ... #Ibeere #Yoruba #Owe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ire ni oju owo nri ire ni oju ojo nri ire loni ori wa afi ire eledua koni je ki a se ise f
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo orin yorùbá laapapo gbefun yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ó ku 'Yiiri rẹ̀ wò'
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ bá mi kírà fún màmáà mi. Òrìṣà bí ìyá o, kò sí láyé. Ẹ bá mi kírà fún màmáà mi, òòṣà bí ìyá o, kò sí láyé 🎼"""" #AyajoOjoIya #Yoruba https://t.co/VbfRdVFlRt
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣe àlàyé òwe yìí : à ti gbé 'yàwó kò tóó pọ́n, owó ọbẹ̀ l'ó ṣòro. #ibeere #Yoruba #Owe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orukò mi ni òlatunji òmò adeyèmì òmò bibi isalè eko isè mi ni sise eeto òrò aje ilu ati onisowo ti gèèsi npe ni economist
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
haha òyìnbó ni iphone mi o kò mọ gb pè yó gba ibi ire o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oun ire la ó máa bára ṣe, a ò ní ṣe'dàkejì #amin #ase
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ẹyẹkẹ́yẹ bá gbìdánwò láti fi enu ṣán Ìjàpá pẹ́rẹ́n, yóò ba ẹnu ara rẹ̀ jẹ́ lásán ni nítorí ahun ẹ̀hìn rẹ̀ t'ó le bí òkúta. #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user. Ko si alaye kankan ju pe osise melo ni ile se alawusa lo le san owo yi lori omo…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Akọgun ni họwu, àdájà l’ogun aye, a kii bani j’agun aye. #Yoruba #YorubaPoem #OgunLaye
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fẹ́ sọ fún wa ipa tí alátagbà kó ńnú ìjọbaàwaaraawa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọpẹ́ ńlá, pírí lolongo ń jí, mojí ire, araà mí sì le ju tànàá lọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọmọ wọ̀nyí sun ẹkùn, wọ́n ké sí ìyá wọn lọ́rùn pé kí èyun ùn pèsè omi fún àwọn. Ara Yewa ò gbà á. #ItanOdoIyewa #IyaRere #AyajoOjoIya
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sing along ori ori o olajumoke lo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orí l'ẹja fi ń labú já, orí làkèré fi ń wẹ̀ l'ódò. Oríi mi à pere, oríi mi àpésìn. Orí l'agbeji ẹni. Ǹjẹ́ kí la à bá bọ̀! #Iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
igboro ti daru eni wo ankara lo ma je semo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kí ni oríkì rẹ ọmọ ìlú wo ni ẹ́ ṣé o mọ oríkì ìdílée tàbí orílẹ̀ rẹ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eseun gan a ki yin fun akitiyan yin awa na o ni sere legbe peturolu rara
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Eyin omo Nigeria rere. Ekaaro. Ajirebi. Loni, Ise kekere owo nla ni aje ti gbogbo wa . Ashe ni ti olodumare #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ naija ẹ yéé bára yín jà ẹ máa bára yín jẹun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àbá má ṣe gbọ́ ti ẹlẹ́gàn bí ó bá ùn ọ̀ láti ọkànàn rẹ o jẹ́ yára ṣe é kó tóó pẹ́ ó ṣe é ṣe kó jẹ́ pé ibẹ̀ ni ògoò rẹ wà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A kú ọdún tuntun o. Àjíǹde ara yóò máa jẹ́ @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ogo f'Olorun l'oke orun :) RT @user: @user @user Ọlọ́run fún yín ní ẹ̀bun sọ̀rọ̀-sọ̀rọ̀ àti orin kí ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìgbàgbọ́ asán ni ohun gbogbo tí ó bá ti jẹ́ ti ìbílẹ̀ lóde òní. Àwọn alákọ̀wé á ní SUPERSTITION ni. Síbẹ̀, ẹ̀ṣẹ́ kì í déédéé ṣẹ́, torí afọ́jú ni òjò ṣe ń ṣù. Kò sí èyí tí kò ní ìdí nínú àṣà ìbílẹ̀ Yorùbá, àìmọ̀kan àti àìláròjinlẹ̀ tó ní í ṣe wá.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oruko mi ni olumuyiwa omo akanmuibadannile oluyoleilu ogunmolaolodogbo keri loju ogun ilu ibikunle alagbala jayajaya
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìpè kan ń dún o, ìpè ìbéèrè Yoòbá sì ni. Ǹjẹ́ o gbá múṣémúṣé nínú ìmọ̀ èdè rẹ? Bí ó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni, bọ́ síbí kí o f'ara hàn! #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
má gbàgbé nǹkan ẹ rántí wípé oun a ní là ń gbé lárugẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Alágbára ń ṣubú | #Spain #idanoripapa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n á ní """"""""""""""""you are old school"""""""""""""""" bí o bá ń fẹ́ ṣe nǹkan ìwáṣẹ̀, tàbí àṣà ilẹ̀ẹ wa. #YorùbáRonu
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré Nigeria Prince tayọ nínú ètò rẹ̀, èyí losi jẹ kí o jẹ àfikún sí àwọn eré ti o nííṣe pẹ̀lú ọ̀ràn
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
èyí ni pé ẹ̀mí ọba tẹ́lẹ̀ wà nínú ọba tuntun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọkùnrin dáfídì ní gbogbo wón
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo fi àsìkò yìí kí gbogbo àwọn ọmọdé àgbáyé kú ọjọ́ òní ọmọ niyì ọmọ lade ọmọ nidẹ́ ́ọjọàwọnèwe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Esù (Ogo Elegba) Metropolitan Museum of Art #esú #exu #legba #escultura #art #africa #yoruba #metropolitanmuseumofart https://t.co/PobflcCe3o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bẹ́ẹ̀ ni @user, Ọ̀gbẹ́ni Arégbẹ́ṣọlá ṣe púpọ̀ ní t'ẹlẹ́kọ̀ọ́ dé @user @user http://t.co/E0hV4QSqYA @user #Osun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mò ń bọ̀ - I am coming cc Alámọ̀já Yorùbá #learnyoruba #yorubawords #yorubaforbeginners #learnyoruba #onlineyoruba #learnyorubaonline #languagelearning #languageteacher #learnnewlanguage #yorubatutorials... https://t.co/uNDYt9GSO4
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ipele eré tó dára. . Mo gbádùn eré yìí. Gbogbo òṣèré ṣe dára dára mo ṣì gbádùn wíwò ẹ. Ó wù mí kó sésìn tó pọ̀. Mo ń dúró de sésìn tó kù.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Nígbàtí ó di 1788, a dá ẹgbẹ́ African Association. Ète ẹgbẹ́ nì ni láti mọ tinú-tìta Ìwọ̀ Oòrùn Afrika àti agbègbè odò Ọya. #Nigbatiwonde
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìwòrìwò làgbàdo ńwọlẹ̀ igba aṣọ ní í mú jáde | ire kànkà ire rìbìtì ire ẹ̀rìmọ̀ ire fẹ̀nfẹ̀ n tiwa lọ́dún yìí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
pẹ̀lú agbéfìtílà (tí gbogbo ètùtù náà ṣe ojú rẹ̀) ni wọ́n ma sin pẹ̀lú ọba náà, láti lè jẹ́ òjíṣẹ́ ọba ní ọ̀run. Àmọ́ àṣà yìí ti dópin tipẹ́, tí wọ́n kò sin Ọba pẹ̀lú èèyàn mọ̀ọ́, ṣùgbọ́n, pẹ̀lú ẹṣin àti akọ màlúù. Aṣọ funfun àti dúdú ni wọ́n ma fi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré àgbéléwò alágbára to ń fọwọ́ tọ́ni lọ́kàn.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ìbà Olódùmarè, ọmọ-aṣehun-ribiti kárí ayé. Ìbà okó tó dorí kodò tí kò ṣ'ẹ̀jẹ̀. Ìbà òbò t'ó dorí k'odò tí ò ṣ'omi. Ìbà là á kọ́ọ́ jú. Nítorí bí olú igbó bá jí à júbà igbó, b' ólú ọ̀dàn-án bá jí, à júbà ọ̀dàn. Mo sùn mo jí ire, ǹjẹ́ kí tún ló yẹmí bí kò bá ṣọpẹ́!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
óbèrè dada ṣùgbọ́n ó túká ósì sun
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
awa aye lati wa sin oloorun wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láì sí wípé, àwọn Ìgbìmọ̀ mẹ́ta yìí fi ọwọ́ so ọwọ́ pọ̀, kò sí òfin tí wọ́n lè fi lélẹ̀, tàbí kí wọ́n yí padà. Orísun: Samuel Johnson, The History of Yorubas
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yorùbá adage for the week: """"""""Àdánìkànrìn ejò ló ń jẹ ọmọ ejò níyà"""""""" Translation: The lone movement of a snake exposes it to danger. What is this Òwe telling you? #learnyoruba #wisesayings #owe #mondaywisdom #yorubalessons #yoruba https://t.co/Wkivci5wDv
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣálúgà, wá ṣá mi lọ́gbẹ́ ire owó, kí n máa r'Ájé ṣe. Sọ mí di Arówólò, kí n di Arówóoyè. Gẹ́gẹ́ ni yóò ṣe láṣẹ Elédùmarè. #iwure #OjoAje
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gẹ́gẹ́ bí ìwádìí ti ṣe fi hàn; = ìdá 76 ọkùnrin ní í gba ẹ̀mí ara rẹ̀ = ìdá 85 ọkùnrin ni kò nílé lórí = ìdá 70 ọkùnrin ni apànìyàn ti pa = ìdá 40 ọkùnrin ló ń jìyà ìlònílòkulò nínú ilé. #IMD https://t.co/PcP0e2Nw37
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìlù ilẹ̀ẹ wa drums of our land
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo mọ̀ pé ọjọ́ òní á dára púpọ̀. #TweetInYorùbá #TweetInYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀kan lára òṣìṣẹ́ Aláàfin Ọ̀yọ́ kan tí a ò bárúkọ rẹ̀ nínú àlàyé tí a gbà ni Òkòló í ṣe. Iṣẹ́ẹ rẹ̀ ni láti pa koríko fẹ́ṣin ọba. #ItanDowe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ewu ò ní wu wá, bí a ṣe ń wá oúnjẹ oòjọ́ lọ, ọ̀nà ò ní nà wá. Àlọ ire, àbọ̀ ire @user @user @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ewé igi àsofẹ́yẹjẹ ni ìyá ń já. Igi àsofẹ́yẹjẹ yìí ní èròjà tí ó ń wúlò fún ìtọ̀jú àrùn ọpọlọ àti ẹ̀jẹ̀-ríru. #Yoruba #Science #Herb https://t.co/bocoRfpNjI
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó yá oko ẹgàn ọ̀rẹ́ẹ rẹ̀ kan tí kò lò mọ́ lo, ó ro igbó orí rẹ̀, ó ná wó, ó ná 'ra kí oko kòkó òun so èso rere. #Itanilumasee
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nọ́líwuùdù ni yóò fẹ́ ní òye tó kéré jù lọ nípa bí a ti ń ṣe sinimá. Àmọ́ ṣá, ó pá mí lẹ́rìn-ín.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user hmmm,ikoko wa fun omi,ohun tun ni a n pe ni amu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user K'éku ilé gbó kó so fún t'oko. Ekú ojú lónà @user @user @user @user @user @user #Yoruba https://t.co/FnE1CG7Zpk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ti dé sí ni wọ́n ma ń sábàá ṣe ọ̀wẹ̀. IṢẸ́ OKO ÀÀRÒ: Èyí ni ọ̀nà tí àwọn àgbẹ̀ tó jẹ́ ọ̀rẹ́, ma ń lò, láti fi kó ara wọn jọ, tí wọ́n ma lọ ṣíṣe lórí oko ọ̀rẹ́ wọn, ní àṣẹ yípo láàárín àwọn ọ̀rẹ́ náà. Iṣẹ́ Ọ̀wẹ̀ àti Ààrò ma ń mú oríṣi ìdárayá wá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Akẹ́kọ̀ọ́ mi ọ̀wọ́n. Mi ò lè dúpẹ́ tán ó. Ẹ ṣé gidi gan-an https://t.co/Bgf7cTcYdA
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olobó ta Ṣàngó wípé Ògún ń gbé ìjà bọ̀, ni Ṣàngó yára f'ẹsẹ̀ fẹ́ ẹ, ó ku Ọya. #OsuOgun #Ifa #Yoruba #Ogun7
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jẹ́ kí ń fi èrò mí hàn. . Eré lo pẹ̀lú àwọn a dojú kọ ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà dojú kọ, bó ti rí owó ọ̀ ṣe kókó ìwo ṣá ti ṣe orí rere. Ìṣe takuntakun lá to wó Gabriel, dájúdájú ó jẹ́ ìkan lára àwọn òṣèré wa tó dára jù.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Òtútù mú to jẹ́ pé. Àwọn ẹiyẹ gan-an nyooru lẹ́nu.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èèyàn 3% fẹ́ ìjọba rere, kí ìṣẹ́ wọ̀'gbẹ́, kí ìgbèríko di ìgboro. @user #Nigeria #Centenary
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orísun =► spring {omi orísun là ń mu = spring water is what we drink} #InYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
olulana awimayehun onibuore afunni ma siregun atogbojule jagunjagun ode orun eru jeje leti okun pupa eleda atererekariaye
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A lè ní """"""""""""""""@user ma ń tèlé gbogbo obìnrin bíi ajá"""""""""""""""", tàbí kí a gbọ́ """"""""""""""""yé é jẹun bíi ajá"""""""""""""""". #Yorùbá #Animal #Metaphor
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìran gàmbàrí ló kó ẹṣin wá ojúọjọ́ọ ti wa níwọ̀oòrùn gúúsù níbi ò fi bẹ́ẹ̀ dára fún ìsìn ẹṣin mọ́là ní í ṣètọ́jú wọn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
alágbára má mèrò baba ọ̀lẹ ni translation a powerful person who does not think is a weakling
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train