text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
#YORUBA Iforowanilenuwo 🗣️. Oyaaaa edibo fun Nigeria 🇳🇬 abi ki edibo fun Oduduwa Republic. Yoruba awa ologbon dori eja mu👇👇 #TweetinYoruba https://t.co/5klxrLBHrT
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àtiṣe pọ̀ jọjọ. Olódùmarè ràn mí ṣe, ìrànlọ́wọ́ọ̀ Rẹ ni mo tọrọ.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: Lọ́jọ́ òní ijó àjólọsíwájú ni, a ò ní jó àjórẹ̀hìn. Lágbára Olódùmarè. #adura"""""""" Amin oh! Mo se amin, mo ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìkàọ̀dàn tí wọ́n sì fi ìjàyè ṣe ilé àgbé wọn wọ́n fi dádò ṣe olórí wọn ní ìjàyè àmọ́ dádò kò tiẹ̀ ní ìfẹ́ sí kí a ma ṣe ètò ìlú tàbí ètò fún iṣẹ́ àgbẹ̀ àwọn tó mú iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣe ọ̀lẹ afàjò ni dádò pè wọ̀ọ́n ìwà rẹ̀ dé góńgó fún àwọn ọmọ lẹ́yìn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user kini itumo ojo riru"""" ọjọ́(rí)rú #Ojoru #Wednesday #InYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ni ile ayé ti ọmọ iya meji ti n p’ara wọn nitori ogún. #OgunLaye #YorubaPoem #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Wọn ò ṣe kúkú darapọ̀ mọ́nra wọn kí wọ́n di orílẹ̀ kannáà?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Happy birthday to you akẹ́kọ̀ọ́ mi @user Ìbùkún Olúwa ò ní fi ọ́ sílẹ̀ nígbà kankan. https://t.co/dSMBrbrPFu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#OmoYoba n ki yin o, àárọ̀ a gbe wá o, ọjọ ti là, owurọ kùtùkùtù a ti wá l'ẹ̀hìn o #Amin #ekaaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọbùn wẹ ọmọ pàṣà gbe pọ̀n, inú èèrí lò ń gbé. Ìwọ yìí là ń rí ńgbogbo #party, tí wà á ru gèlè yẹyẹ #Lagos #Sanitation
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kò sí ohun titun lábẹ́ ọ̀run bí ó sì ti ṣe wà ní àtètèkọ́ṣe ni yóò máa wà títí láé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ohun to wa seni laanu ni wipe awon ti a gbemi le lati sooto ohun ti awon naa o je k
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bade de ade obaa o ba deobo oba n ho idia o ba ho���� my childhood
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Torí ìdí èyí, wọ́n ka Ṣàngó sí alágbára, abàmì, ọlọ́gbọ́n ènìyàn tí ó ri ṣà #orisa #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni tó ṣe ohun tó dun'ni lóòní, lè ṣe ohun tí yóò dùn mọ́'ni lọ́la. / A person who hurts one today may still be a blessing to one tomorrow. [No closed case: write-off no one; be positive and be open-minded: don't get shackled with vindictiveness.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user @user @user nikan lo le gbawa lowo awon agbaya wọn…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ilé ọmọ rẹ̀ fẹlá èyí tí ó mú olúfúnmiláyọ̀ wọ inú ipò àìjáráayé àìjáráọ̀run èyí tí ó fi wá pàpà mú ẹ̀mí ìyá olúfúnmiláyọ̀ lọ ní oṣù igbe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aládùn, ó sì jinlẹ̀ ju bí mo ṣe rò lọ.. . . . Eré ti wọ́n kọ dáradára, ó sì jẹ́ ìdàpọ̀ tuntun mọ́ iṣẹ́ Nollywood
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Òkú ní owó, òkú kò ní owó, òkú yóò náwó Ó ti di dandan kí òkú ó ná owó Ahun kìí gbó kí ó máà yọrí Ẹ̀yin t'ó ni ayé, ẹ yọ orí èmi Adéṣínà ọmọ Owókòníran sí rere. #iwure #OjoAje #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láyée ọyẹ́, ààjìn ni ọyẹ́ ti ń jáde, fẹ̀ẹ̀rẹ̀ ò kí ń ṣe é kó, òtútù ọyẹ́ a máa mú kí oorun rọ 'ni lọ́rùn gidi gan-an ni. #Layeoye #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tó yá ẹgbẹ̀fà, tí ò san án, bẹ́ igi dí ọ̀nà egbèje ni. / Whoever borrowed a small sum, but refused to repay it, h…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Iru wahala wo le 'yi bayi iwo olorun. Kilode.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí là bá bọ à bá fòòṣà sílẹ̀ orí ló ń gbé ni dé ibi gíga orí ní í gbé ni délé owó orí mi gbé mi débi ayọ̀ mi wà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user hahahaha. Ti ayé àtijọ́ mà ni o. Bí wọ́n ti nṣe kí àwọn òyìnbó àti Lárúbáwá tó dé.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
emo wolu iwo ni ipinle osun abdulrasheed adewale akanbi ti fe ja si oja e mu so o ki oba alade ile yoruba ma so isokuso pe oluwo ilu iwo ti di oye itan akanbi ti yi oye oluiwo si emir ile yoruba nje ko kin se aisan opolo lo ya wo aafin oluiwo ilu iwo bayi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ronú àti ṣe Indomie láìsí oun àdídùn. Eré yi kò da débi pé, óku díè kó parí nkò mọ oun ton sẹ̀lẹ̀.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bí ọmọ yín bá darapọ̀ mọ́ wa, lẹ́yìn oṣù mẹ́ta, yíò le kà, kọ àti sọ èdè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ni yíò tún le kọ́ láti le kọ èdè Yorùbá dára dára lórí ẹ̀rọ káyélujára. Fún àlàyé ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, ẹ kàn sí https://t.co/0T2N3tBJi6 #Atelewo #Yoruba #Onlineclass #zoom a Tunde https://t.co/Kh9oEorcvA
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìyẹn bẹ́ẹ̀, ẹ dákun @user, mo mọ̀ wí pé ẹ ti rí ìwé àpilẹ̀kọ ìfẹ̀sùnkàn tí àwa ọmọ Áfíríkà nílé l'óko fi ṣọwọ́ sí i yín. Bí ọmọlúwàbí tí ẹ jẹ́, máa rọ̀ yín kí ẹ gba ohun tí ó wà nínú ìwé náà rò, nítorí ọjọ́ òní kọ́, nítorí ọjọ́ ọ̀la ni.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni tí kò tó ni í nà tó ńdè'nà de’ni, àjẹkún ìyà ni yóò jẹ. / Whoever cannot defeat someone in a fight, but decides to waylay the person, courts severe purnishment. [Exercise self-control; don't be presumptuous.] #Yoruba #proverb
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tí kò bá lè jìyà tó kún ahá, kò leè gbádùn ọrọ̀ tó kúnnú àmù. / Whoever cannot endure a cup-filled deprivation can…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: ORÍKÌ ÒGÚN Ògún lákáayé, ọṣìn mọlẹ̀, Onílé kángun kàngun ọ̀run, Ò ní omi nílé, ó fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀, Ò ní aṣọ nílé, ó fi imò b…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
4. Irú àwọ̀ wo ni à ń pè ní 'Adíkálà'? A) Àwọ̀ tí ó ní ìlà B) Àwọ̀ tí ó ju ọ̀kan lọ D) Àwọ̀ dúdú bọ̀lọ̀jọ̀ #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Níṣe laláṣọ ogun ń gba ojúnà BRT, LASTMA ò sì mú wọn, b'ẹ́ni ò lẹ́sẹ̀ńlẹ̀ bá ṣ'àfarawé pẹ́rẹ́n, ó k'ẹ́ran. @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ẹyẹ oko ò mọ bíntín lọ, eré e kó kọ́lé ló máa máa bá kiri. / No matter how tiny a bird is, its attention will be riveted on building its home (or nest). [Focus on tangibles not trivialities; don't major on minor things.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òní á sàn wá, ọ̀la gan-an ò ní ṣaláì sàn wá. Ire ni ti wa lọ́dún tuntun. #Amin #Ase
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àìsanra tó ajá ológìnní kì í ṣe ti àìjẹun ká'nú, bí'ran rẹ̀ ṣe mọ ni. / Cats relative smallness to dogs isn't for want of food; that's how cats are. [Appearance can be deceptive; respect what at first sight is not clearly obvious.] #Yoruba #proverb https://t.co/HWooqbcZCZ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
buredi agege wa naa wa nbe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àlọ́ o àlọ́ mi dá lórí òṣùpá àwọn ọ̀tá gbógun títí wípé kí òṣùpá ó máà tànmọ́lẹ́ ká ayé àmọ́
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré Sinimá tó dára jù lọ. . . . Things Fall Apart jẹ́ eré tó dára jù. Kódà, ó dáa ju The Force Awakens lọ. Ó yẹ kí ó ti gba Oscar márùn-ún, ó kéré tán. Òkónkwo jẹ́ okùnrin tí ó wuni jù tí mo ti ríí, béè sì nìyí, gbogbo àwọn tí mo ti pàdé tí wón ti ríi rí nífèé rè.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
yóò ni kí ẹ máa kọ dípò yíò gẹ́gẹ́ bí òfin àkọtọ́ èdè yorùbá ṣe sọ ohun à ń pè ni kí a kọ sílẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òròmọdìẹ ni ọmọ adìẹ kí ni à ń pe omo kìnnìhún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a rí àpẹrẹ ńnú orúkọ ìró gbólóhùn mélòó kọ̀ọ̀kan ló kàn yàtọ̀ ìtumọ̀ ò yàtọ̀ òrìṣà ni oritṣẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìpínlẹ̀ ògùn tí nawọ́ ìbásepọ̀ sí ilẹ̀ benin lórí isẹ́ àgbẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Awon ara Eko ni won n jere ijoba Aregbesola l'Osun - Fatai Diekola… https://t.co/RuX6Gic26t
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò sí ibi tí a ì í dáná alẹ́, omi ọbẹ̀ nìkan l'ó dùn ju ara wọn lọ. #oWe #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Apẹ ló yẹ kó jẹ́, kì í ṣe àdògán, mo gbé ọ̀rọ̀ mi jẹ. Ìkòkò apẹ irin, àrìrò tí a fi irin ṣe ni àdòg…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O ò ṣe wo ibi iṣẹ́ àwọn bàbá wa wọ̀nwọ̀nyí, mú ọpọlọ ìwé kún un, kí o ṣe é lọ́nà àrà ọ̀tun. #IseTiYorubaNse #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Iléeṣẹ́ ètò ọ̀gbìn ìlú Èkó rọ bàbá àti màmá Ẹ̀kọ́ pé kí wọ́n ó lọ kọ́ iṣẹ́ àgbẹ̀, pé ilẹ̀ wà f'ẹ́ni fẹ́. #IseAgbeNiseIleeWa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nínú àwọn ìlú ilẹ̀ yoòbá tí ó jẹ́ igbó kìjikìji ìpínlẹ̀ ògùn jẹ́ ọkàn ìdí kan sì nìyí tí òrìṣà òṣóòsì fi gbayì ńbẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ken ọkọyàwó o kú oríire o barbie ìyàwó wa wàá bí ìbejì
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kàkà kí n yan àlè ma gbólóbìnrin wálé á daya lọ́ọ̀dẹ̀ mi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ida lohunlohun... Ki i je ka mu biledi koja legbe eti e.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ò ṣe dán an wò ná. @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orisun je ibi ti nko ti jeyo orisun omi mio mo eyi tioku rt bá mi dáhùn yìí =
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọlọ́tọ ní t’òun ọ̀tọ̀. . Èyí kìí se àwọn sinimá gbẹ̀ẹ́gbẹ̀ẹ́ ojojúmọ́ o. Àwọn gbajúmọ̀ òșèré inú rẹ̀ tọ́ sí àmì ẹ̀yẹ fún ipa tí wọ́n kó. Gbogbo Ìșẹ́jú inú rẹ̀ ni mo fẹ́ràn. Jọ̀wọ́, wò ó!
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user eye to nfo l'oke, eja inu ibu, pelu koriko, gbogbo won lo ns'ope f'Eleduwa, a dupe o, #ekaaro o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♫ Àjàlekè lọ̀ṣíbàtà fi lekè odò...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Oro naa t'oju su ni! Gbaga!! Onijekuje jegudujera ma po ni orile ede Naijiria o! Afi k'edumare ko …
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀kan nínú àwọn ìtàn àtẹnudẹ́nu fi yé wa wípé àwọn Ìjẹ̀bú jẹ́ ọmọ Ọbaníta. Ọbaníta jẹ́ ẹni tí Olówu lò láti fi rúbọ Ìtàn náà fi yé wa wípé, Olówu lo èèyàn láti fi rúbọ l'óríta, tí ẹbọ náà sì jẹ́ ẹbọ-níta Níbi tí wọ́n ti fẹ́ fi rúbọ, wọ́n fi sílẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbàmí gbàmí ọlọ́run ọba ìwọ ni mò ń ké sí ọ̀gbàgbà tí ń gba ará ilé tí ń gbará oko
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilé ayé nyí lọ ribiribi bí òkúta. Ọjọ́ ajé mà tún dé o!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
toju iwa re ore mi jf odunjo toju iwa re ore mi ola a ma si lo nile eni ewa a si ma si lara enia olowo oni ndolosi bo dola okun lola okun nigbi oro gbogbo won
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òjíjí bá mi jí wọn kí wọ́n máa mú owó wá. #iwure #OjoAje
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ewúré jé eran ilé. G, Gb, H. On our Episode 4 of Kó Omo re with @user #Yoruba #subtitled #Ede #Asa https://t.co…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni a ṣe lóore tí kò dúpẹ́, bí ìgbà tí ọlọ́ṣa ko ni lẹ́rù lọ ni. / To be kind to a person who isn't thankful is akin to being robbed by a thief. [Attitude of gratitude is it; be ever thankful.] #Olaicetv #Yoruba #Olaiceman #proverb
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá àtijọ́ ni pé ìdákan orí eni mbẹ láíyé, Idákejì mbẹ lọ́run. Ìyẹn ni Ìpọ̀nrí. @user Ẹ làwá lóye o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní kété tí fojú ba yèyé rẹ̀ inú rẹ̀ dùn rékọjá àlà ó dì mọ́ ọn tímọ́ tímọ́ ọmọ rọ ìyá kí ó dúró ti òun láàfin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù tí a pilẹ̀ ṣe ni Áfíríkà lórí àwọn ará Áfíríkà ni. Ìyàtọ̀ tí ó dára.. . Ó tú ni lára láti wo fíìmù tí wọ́n ṣe ní ilẹ̀ Áfíríkà tí ó sì dá lórí àwọn ènìyàn Áfíríkà ti òde òní yàtọ̀ fún ògbójú ọdẹ òyìnbó àti ìgbà ìmúnisìn
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
àjọkẹ́ mi ìyẹn ni mi ò fẹẹ agbára mi ká a owó sì rẹpẹtẹ ní ọwọ́ mi mi ó fẹẹ ìrànlọ́wọ́ láti tọ́jú ẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òrìṣà òkè jẹ́ ki npé meji obinrin kò dé inú – Àṣà Ìkó-binrin-jọ: “The prayer of a woman to the god of https://t.co/pRo8yAe4Jt
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí la ó ti ṣèyí sí?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ní òpin kò ṣé iṣẹ́dúró. Ṣíṣẹ takuntakun láti yàgò fún ìdọ̀tí yìi láíláí; àti lórí Amóhùnmáwòrán .
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ṣé Yoòbá ní 'Ìbànújẹ́ ò sí fún ẹni eyín rẹ̀ ta síta, ẹ̀rin ni ní gbogbo ìgbà' :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user E jowo e maa tesiwaju. A ngbadun yin. Eseun. @user e jowo e #tele mi pada. Oodua a gbe wa o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oonirisa Ọba Adeyeye Ogunwusi Ọba tó ń gbadobale Ọba Ooni Ilé - Ìfẹ́ tí kéde Olórí tuntun láàfin. Ooni so èyi di mímọ̀̀ yìí lórí atejise instgramu rẹ láti kéde aya tuntun náà tí ó pè orúkọ rẹ̀ njẹ Shilekunola Moronke Naomi https://t.co/bXdpcJs1q8
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jọ̀wọ́ wọ inú ilé, kó àwọn ẹrù rẹ, kí ò sì fi ilé yìí sílẹ̀ báyìí!. . Èyí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn sinimá tó burú jáì jù tí mo ti wò.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
yoruba ibadan yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìpele ìpele ni ilé ayé get up
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ro ju di e na loku, emi asika osu 🙏🏼😇 #TwitterYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Agbe máa gbóhùn mi re òkun, alùkò máa gbé ohùn mi re ọ̀sà. Ẹ̀yin abiamọ ayé, ẹ̀yin abiamọ ọ̀run, ẹ wá dúrótìmi lẹ́hìn kó yẹmí. #AyajoOjoIya
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn to lewa ti o ṣàfihàn àṣà ilẹ Nàìjíríà. Ìtàn náà yàtọ ti o sí nira lati lè mọ ìparí rẹ gẹgẹ bi awọn eré Naijiria miiran. Agbọdọ wo ni eré náà
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
mo towotowo ki awon omo yoruba nibi gbogbo lorile ede ni ipinle ati loke okun ajuwa se oooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: Mo fẹ́ràn bí àwọn Èkìtì ṣe má nsọ Yoòbá :) Èdè Èkìtì ló dùn ún kọrin jù!!!"""""""" Ati Ijesa na pelu!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mi ò fọwọ́ rẹ̀ sọ̀yà. Ìtàn tó dára gidigidi ni ṣugbọn àwọn ẹ̀bùn tí ò sọ kò kún tó.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
egbe ilu ikare akoko yewo awa ni omo oloke meji ta ko ta bo oke owa ale oke baba wa yoruba re wa https
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ire mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yóò kan ẹní fẹ́ 're lọ́sẹ̀ yìí. Ire owó. Ire ọmọ. Ire ara-líle. #iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tí bíńtín ò tó, púpọ̀ yóò jìnnà sí i. / Abundance will be far from whoever is not contented with a little. [Conten…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn bàbá wa mọnimọni mèèyànmèèyàn pòwe wọ́n ní bí ọkọ̀ bá ròkun bó rọ̀sà ó di dandan kí ó forí lé èbúté ǹjẹ́ o lè sọ ohun tí à ń pe ẹ̀yà ara ọkọ̀ ojú omi ní èdè yorùbá = ìdákọ̀ró
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kosi ohun to soro se fun eni to ba ni ipinu"""""""" #TweetinYoruba #Yoruba https://t.co/EX9gon9GMH
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Agba wa bura.......
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user e je bo si igboro. @user ko ni ibo wa o @user ti wo inu igboro Eko, Agege, Alimosho, Agbajandi eti be be lo. Awon ara bi lon gbo wa zo bia, ibo wan o le gbeyin de ori alefa, e ma se asise ti e se ni 2015 ti e da awon Yoruba nu lo darapo mo awon ore wa ni Alaba https://t.co/oeRTO5jGfs
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ojúmọ́ o mo kí gbogbo ọmọ naija kú ìpalẹ̀mọ́ èto tòní gbogbo ẹ̀ á lọ ní ìrọwọ́rọsẹ̀ o lọ́lá ọlọ́run ọba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bíkòṣe ìyànjú òyìnbó láti pa iṣe wa run pẹ̀lú ètò tí yóó mu wa gbàgbé àṣà baba ńlá wa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Amin o mo dupe e ku igbadun ilu wa yii o""""""""@user: @user emi naa ti n tele yin o, a ko ni tele ara wa wo inu iparun o! E kaaro""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ilẹ̀ àánú olúwa kì í ṣú gods mercy never runs out no impossibility with god he cannot be contained or cornered
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ní ọjọ́ kini oṣù kẹjọ, ayẹyẹ Ijade mú ká rí ọpọlọpọ àwọn ènìyàn ju ẹyẹ àwọn ẹni ta n'reti lọ.. . . . Eré orí ìtàgé yìí jẹ eré tó sọ nípa bí àwọn ènìyàn tó ngbé ní àwọn ìlú tó lajú diẹ ṣe ngbiyanju láti lè bọ́ lọwọ ìgbé ayé wọn tí tẹlẹ àti bí gbé ayé wọn tẹlẹ ní ṣe pẹlu ọjọ ọla wọn.. . . . Níbi ayẹyẹ Ijade ile ìwé,...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
SOME YORÙBÁ ÒRÌṢÀ & ANCESTRAL SPIRITS, AND THEIR ODÙ IN IFÁ / ÀWỌN ÒRÌṢÀ YORÙBÁ, ALÁLẸ̀ YORÙBÁ ÀTI ODÙ IFÁ TÓ ṢẸ̀DÁ WỌN (1): Ṣàǹgó - Ọ̀kànràn Ògún - Ògúndá Èṣù - Òdì Eégún - Òtúrupọ̀n Ìbejì - Èjì Ogbè
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àánú ojú kì í jẹ́ ká tọ́wọ́ bojú the respect one has for the eyes wont let one poke fingers into them
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
igba a ba ti ji saye lowuro eni kutukutu ki i joni lese bi osan ire nile ire loko
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo wólẹ̀ o ọ̀gbẹ́ni akínwùnmí adéṣínà mo kì í yín mo kì yín bákan náà ni mo gbé òṣùbà sàńdákátà fún un yín fún àwọn iṣẹ́ kantikanti tí ẹ̀ ń gbé ṣe ní ti ìgbésókè ilẹ̀adúláwọ̀ ẹ sì kú orí ire ìyànpadà sípò gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train