text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Ta ni Ọmọ Ògún? L'étí omi Ògún ni a ti máa ń ṣe ìtẹ̀bọmi fún ọmọ Ògún, a ò sì bọ̀ wọ́n ní ìyẹ́ àlùkò fún ọjọ́ méje. #OsuOgun #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àroòdákẹ́ Ka ṣá máa wòran ni báyìí. Ẹ̀yin lẹ dìbò yan ṣéǹjì. Ẹ yáa máa gba ṣéǹjì yín ǹṣó🤣 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọjọ́ kan, ọ̀rọ̀ kan | One word per day • Ìgbà - time • Follow us @user for daily Yorùbá contents! • • #igba #time #newyear #yorubamovies #yoruba #nigerianweddingsinamerica #yorubaindiaspora #yorubaclasses https://t.co/rtqecYpCfp | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bẹ́ẹ̀ ni bẹ́ẹ̀ ni arákùnrin wa àgbájọ ọwọ́ la fi nsọ̀yà o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
BIRDS IN YORÙBÁ / ÀWỌN ẸIYẸ NÍ YORÙBÁ: WILD PIGEON - ÒRÒFÓ AFRICAN PIED WAGTAIL - OLÓGẸ̀SÁ WEAVER BIRD - Ẹ̀GÀ ALLIED HORNBILL - ÀTÍÒRO https://t.co/fwYdBib0nR | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí a kò bá dẹ́kun ìgbìyànjú, bó pẹ́ bó yá, akitiyan á dópin lọ́jọ́ kan. / If we won't quit trying, our hustling will one day come to an end. [Giving up too soon is the bane of success: persistence is it; if we won't quit, we will win, eventually.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ tó ń kọ́ iṣẹ́ ní abẹ́ wọn, ní oye ọdún tó ma lò, láti fi k'ọ́ṣẹ́, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ náà bá ṣe le sí. Bí àwọn ọmọ ẹnu ìkọ́ṣẹ́ bá ṣe ń pẹ́ ní ẹnu iṣẹ́, ni wọ́n ṣe ma ma mú iṣẹ́ ṣe fún ọ̀gá wọn. Lẹ́hìn òmìnira àti ìyànda lẹ́nu iṣẹ́ kíkọ́, | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ̀yin olólùfẹ́mi ẹ káàárọ̀ o lónìí ọjọ́ kejì oṣù ògún oṣù tuntun a ò ní kú a ò ní rùn ẹ̀mí wa á la ọdún yìí já | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Mi o le ka nko ti o ko , katowa so wipe mo fe mo itumo ee #TweetInYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Bẹ́ẹ̀ ni, àmọ́ àwọ̀ ni à ń sọ nípa rẹ̀. Àwọ̀ wo ni ti Ògún? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
gbogbo ẹ̀ dọwọ́ baba lọ́kè | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
In Yorùbá ìyẹ̀wú is indoors/inner room (jẹ́ ká wo ìyẹ̀wú lọ - let's go indoors) #InYoruba #learn #yoruba http://t.co/Io3TGwOm9l | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
BBC News Yorùbá | Ọkọ ìyàwó ẹlẹ́kún: N kò bá tí ba ẹnu jẹ́ lọ́jọ́ ìgbeyàwó, àwàdà ni mo se - https://t.co/juGdc4Qot9 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọlọ́run ní ká máa jẹ ká máa mu ká sì máa yìnbọn ìdí | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fún ọjọ́ márùn-ún gbáko ẹ óò máa jẹ̀gbádùn onírúurú egbòogi ti wa t'ó kápáa kòkòrò-àìfojúrí bakitéríà. #waaw #Antibioticresistance @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé, àwọn bàbáa wa máa ń fi irun ara ehoro ṣe oògùn tí ò ní jẹ́ kí iná ó jó? #ScienceYoruba https://t.co/qc2k9zg0et | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹní bá fi iṣu tí kò jinná gún'yán, o di dandan kó jẹ iyán tó lẹ́mọ. / Whoever prepares pounded yam with yams that are not fully cooked, will certainly eat lumpy pounded yam. [Patience is it: good things take time; don’t force issues before their time.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eni Aba laba ni BaBa @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ àlè, n'ọwọ́ sókè! | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ikan ni inu awon akorin ni psquares paul okoye ti ja iya omo re keji sile ni ile iwosan | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bí mo ṣe máa nsọ̀rọ̀ ní ojojúmọ́ nìyẹn àfi ní ibiṣẹ́ gẹ̀ẹ́sì nìkan ni gbogbo wa gbọ́ níbẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fídíò Oríkì Ìkòròdú |#EdeYorubaDunLeti #Yoruba #Nigeria #SaturdayNight #SaturdayVibes #SaturdayThoughts #SaturdayMotivation @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user https://t.co/QqzmkX7kph | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
toò èmi dúpẹ́ lọ́wọ́ elédùà pé ọjọ́ òní tún ṣojú wa a ta á bí i tẹ́tẹ́ ní èsí pé a ó ṣe ẹ̀míì àmọ́ kò dá wa lójú | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Dárúkọ ẹ̀ya ara ti orí. #Ibeere | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré tí o jáfáfá. . Mo gbádùn ẹ ni gbogbo ìgbà tí mo fi n woo! ìtàn ti o dára. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọba kò ní fìlà adé ni ó ní #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí iṣú tó di iyán a gún iṣu ní odó kò ní dáa fún | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
e gbe ori yin fun awon ti won yo ju | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀? Bí ènìyàn bá papòdà ní ayé àtijọ́, orí odó tí a dojúu rẹ̀ délẹ̀ ni a tí ń wẹ ìwẹ̀ ìkẹyìn fún òkú, ni a ṣe máa ń sọ wípé nǹkan tí ó ti bàjẹ́ 'ti gorí odò'. #Yoruba #AkanloEde #Egungun https://t.co/NvawArerKC | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yorùbá sọra wọn di bọ́ọ̀lù táráyé ń gbá | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Omo end kìí burú burn ká fi fékùn paje. #yoruba #owe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Proverbs 22:28 Máṣe yẹ̀ àla ilẹ igbàni, ti awọn baba rẹ ti pa. Remove not the ancient landmark, which thy fathers have set. #Yoruba #Bible #God | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user @user @user oooo. Àwa mà nìyẹn o. Ẹ kú gbogbo ẹ̀. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fiimu tó ṣàfihàn ìrètí orílè-èdè kan fun àyípadà sinemá tó dára. . . . Ìrètí ni pé àwọn alágbè jáde eré tí ń ṣe tii Naijiria náà le fọwọ́ ṣò wọ́pọ̀ torí ọjọ́ ọ̀la tó dára fún ilé-isé ìgbé fiimu jáde ti ìlú Nàìjíríà. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: @user Ilu Ogbomoso lawa tiwa o..taba j'eka tan a tun m'uko yangan #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ṣé irin a sì máa dógùn-ún tó ba rí afẹ́fẹ́ tàbí omi. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
LAWMA, Visionscape, awọn wo gan lo n kodọti l'Eko? E wo fidio ohun ti awọn eniyan so nibi: https://t.co/wZ3u1WeGca #lawma #visionscape | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìwé ìtàn àròsọ aládùn yìí tí ó jẹ́ apá kejì kékeré ẹkùn kún fún ẹwà èdè ó sì tẹ síwájú nípa ìtàn àlàbí àlàbí rí oríṣiríṣi ìdojúkọ nípa ẹ̀kọ́ rẹ àti ọ̀rọ̀ ìfẹ́ kínni àlàbí ṣe àbi àyànmó ni ṣe àlàbí wá le borí bí | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
gẹ́gẹ́ bíi ìgbàgbọ́ àwọn yorùbá ṣe lọ lórí ìṣẹ̀dá ara ènìyàn ọbàtálá àti ògún ni wọ́n ṣẹ́dá ara ènìyàn ògún ló ṣẹ́dá apá àti ẹsẹ̀ ènìyàn ọbàtálá ló ṣẹ́dá ara ọmọ nínú oyún àjàlá ló mọ orí ọmọ nínú ìyá rẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ààtàn tí kò bá gba ẹ̀gbin, kò ní kún bọ̀rọ̀. / A refuse dump that won't tolerate filth won't be filled up easily. [Be tolerant; intolerance can impose limitations.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tonga: #Yoruba #kasahorow Tonga nwa kinni? Tonga nwa orin kan. Tonga wa 2014 ninu… https://t.co/BOgJkjsKWA #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Yà fún nǹkan kan pàdé nǹkan kan... @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
JAN MOIR: Meghan's got all she wanted and Harry's given up so much https://t.co/JivC6MyyUg via @user 🤔👸🏽😒 Àpọ́nlé ò sí fún obìnrin tí ò ládé orí. / There is no honour for a woman with no crown (her own husband). #Yoruba 👑😬 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìṣó mọ́kànlélọ́gbọ̀n níròó ara ọ̀pá nì dúró fún iye ọdún tí ọ̀rànmíyàn ló láyé ìsó náà dúró fún ọdún lórí ìtẹ́ àti ọmọdún rẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kékeré l'a ti ń pa ẹ̀ka ìrókò; b'ó bá dàgbà tán, kò ní ṣe é gé. Ewé, èso àti egbò igi túdè gbọ́ gìrì ọmọdé. #Yoruba #herbs #EweOmo https://t.co/bkXgZ9s17v | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àmọ́ ṣá, piparun rẹ̀ di ọwọ́ọ kówáa wa. Píparun rẹ̀ ńkọ́, ọwọ́ọ dede wa ló wá. Ọmọ àlè ní í fi ọwọ́ òsì júwe ilé e baba rẹ̀. #OmoYorubaAtata | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#DPO àgọ́ ọlọ́ọ̀pá Èjìgbò ti gba ìwé kúrò ní Èjìgbò látàári ìṣẹ̀lẹ̀ láabi yìí. #AjataOja | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tútù ie ẹja tutu = fresh fish ẹ̀fọ́ tútù = fresh vegetable as used for food new is fresh = titun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: E je ki eni ire seun ni aarin wa:eni ire o le se wa ni jamba;eni ire a yowa ni igba iponju nitori wipe a laanu ni eni ire.@user… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
baba wande omoluabi awon omo mi wa losibitu won fee soperashon igo eje mefawon tun gbese won de o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ipo kelo ni ṣ wa ninu alifabẹẹti yoruba aogun bikọkandilogun dikejilelogun eikọkanlelogune ìkankànlélógún ni o | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó d'òru k'áse ó tó ó wọ̀. #EsinOro🐎 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Èèbó aláwọ̀ funfun báláú kúkú ni. Èmi ọkùnrin mẹ́ta. Wọn ti mọ̀n mí. Oun tí mo wí l'abẹ gé. Ó yínu sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan lójú ẹsẹ̀ ni:) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àdúrà mi fún 2013 ni kí Ọlọ́run Ọba gba àkóso ayé mi. Àtí ti gbogbo yín náà. #adura #2013 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ káàárọ̀ o gbogbo. Ọlọ́run Ìfẹ́ kó máa bá gbogbo wa gbé o. #ekaaaro #ife | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí Ọlọ́run wà pẹ̀lú awọn tí ìjì #Bopha kọlù ní #Philippines àti ib'ìyókù. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jí ire o. Ọmọ Yorùbá, àárọ̀ o! #yoruba #goodmorning | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aworan aashe olododo i ku ni nijeria ewo awako umeh ti o da $ pada nigba ti eni ti ogbe gba gbe re | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
orin àti à̀wọn ipa ohun kò nígbàgbogbo báramu bí ó ṣe pàtàkì díẹ̀ nínú àwọn ìwòye fíìmu náà. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Ojúmọ́ ire ló mọ́n o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orin atunilára tí ó sín pẹ́pẹ́ pẹ̀lẹ́ orin jáàsì àti pọ́ọ̀pù tí ó peregedé àti ẹgbẹ́ akọrin eléré ìtàgé tí ó kún ojú òṣùwọ̀n. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
A ò lè torí ayé dayé ọ̀làjú kí a máa f'ojú egbò gbo ilẹ̀. Ì-ṣẹ̀-ṣe làgbà, ẹ máà jẹ́ a dà á nù bí omi ìṣanwó. #IseseDay #IseseLagba #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èyun-un bẹ́ẹ̀. Wí fún Olódùmarè wípé mi ò lè ṣàì dúpẹ́ ohun ribiribi tí O gbé ṣe nílé ayé mi lọ́dún 2017. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn bàbá wa mọnimọni m'èèyànmèèyàn p'òwe wọ́n ní """"""""bí ọkọ̀ bá r'òkun b'ó r'ọ̀sà, ó di dandan kí ó f'orí lé èbúté.🚢⛵ Ǹjẹ́ o lè sọ ohun tí à ń pe ẹ̀yà ara ọkọ̀ ojú omi ní èdè Yorùbá? ⚓= ìdákọ̀ró #InYoruba #LearnYoruba #Language #Yoruba https://t.co/BtkvuR5vrX | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ounje osan re o @user @user @user @user ...eku igbadun re o https://t.co/b5Rso5OCrR | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó rẹwà.. . Sinimá yìí pani lẹ́rìn-ín gidi gan-an ni. Àwọn òșèré tó mọ isẹ́, àti pé wọ́n rí I ṣe. Owó ìgbafẹ́ tí ènìyàn fi wò ó kò ráre. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ó ga jù. . Fíìmù ‘Citation’ jẹ́ àlọ̀pọ̀ ișẹ́ ọpọlọ àti àwọn òșèré tí ó ní ẹ̀bùn púpọ̀. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
èjì ogbè ló ní kí ó gbè mí | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orúkọ tí a ma ń pe ọba Ìlú Ìlará ni, ALÁRÁ TI ÌLÚ ÌLARÁ. The title of the king of Ìlará is, ALÁRÁ OF ÌLARÁ (LAGOS STATE). | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹranko abìwo ẹranko afàyàfà ẹranko abìyẹ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Nínú oṣù kẹ́jọ tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ yìí, a ò ní rí ogun ẹjọ́, ọmọ aráyé ò ní fi ọ̀rọ̀kọrọ̀ kọ́ wa lọ́rùn. Ẹjọ́ ẹlẹ́jọ́, ọ̀ràn ọl… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Rántí ọmọ ẹni tí ìwọ ń ṣe o 🎼 #Ajinde #IYIL2019 #Yoruba https://t.co/mBu4tW1pTq | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ope, iyin,ati ogo, fun Eledumare oba to ni kokoro aanu lowo, iba fun oba awon oba, HELLO Eledumare oba aj ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òjò ń rọ̀ inú orí ń dùn. Àfi bójò bá tún rọ̀ lọ́la, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ooru ọ̀la ò ní ṣe é kó. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user e se o bee ni yoo ri fun eyin naa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Yoruba Ibaje eniyan koda ise Oluwa duro. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo gbádùn eré náà. Eré tí ó dára tí ó sì ní ìparí tí ó dára yàtọ̀. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
odun ton bo a gbewa sowo a gbewa somo a gbewa is aiku baale oro ati alaafia to pe ye won o ni fi enikankan wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹkùn-Òsì, ni wọ́n ń pè ní Ìkòyí, di òní. Wọ́n fi adébẹṣin jẹ ONÍKÒYÍ ti ÌKÒYÍ. Aláàfin sì pàṣẹ wípé, ONÍKÒYÍ ni kí o ma sin àwọn Ẹkùn-Òsì àti àwọn àlejò pàtàkì tí wọ́n ń lọ sí Ọ̀yọ́, wọ ìlú. Ìkòyí wà ní òpópónà Ọ̀gbómọ̀ṣọ́ - Ìgbẹ̀tì. Ikoyi ni Olú fún Ìjọba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọlọ́run wẹ̀wá mọ́n. Wẹ̀wá kúrò nínú àìṣedédé wa. Dáárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá o. #adura | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eyin eeyan mi ninu oluwa e kaaro oh a ku jimoh oloyin ode ire loni oh rt ó tọ́jọ́ mẹ́ta o al | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Alafia #AlafiaAtiIsokanFunGbogboEniyan #Yoruba #Langbasa #Lagos #Nigerian #African 👏🏼🙌👏🏼🙌👏🏼 Alafia ati isokan fun gbogbo eniyan https://t.co/4KdbaCGVtC | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Dárúkọ orúkọ mẹ́ta tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú 'Lá'. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ni òwúrọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kan, ó tọ́ ìyá-a rẹ̀ lọ láti ṣ'àlàyé ọ̀ràn náà tí ojú-u rẹ̀ ń rí nílé ọkọ. Ó sọ fún ìyá-a rẹ̀, wípé… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn ẹlòmíì ń ko ọ̀rọ̀ inú igi lójú kòrókòró, bá ní gbólóhùn. #EdeAbinibi #Yoruba #IMLD17 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èdè ti pọ̀jù ní naija mélòó la fẹ́ kọ́ níbẹ̀ tí wọ́n bá ṣe bẹ́ẹ̀ ẹ fẹ́ dájàálẹ̀ nìyẹn o ijaw àti calabar ò ní gbà láí láí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ogo!!!!!... Ni fun olodumare. #TweetinYoruba https://t.co/kLF3f5NLST | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eni ti o ba ni iru eni kole mo iyi eni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò síbi tí ìṣe ò sí mò ń wo ètò afẹ̀ríhàn tí ó dá fìrìgbagbòó lóríi àwọn ìgárá ọlọ́ṣà orí ẹṣin ní britain nínú ọgọ́rùnún ọdún kẹtàdínlógún th century ẹní bí olè kò bímọ àwọn àgbà ló wí bẹ́hẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ara won ni mi | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
lámọhín táa jọ fẹ̀gbẹ́lẹ́lẹ̀ lánàá ti lọ sísà òṣùba sàdáńkátà fún olódùmarè mo dúpẹ́ mo jíi re | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó ti wá di iṣu ata yánanyànyan ní àwọn agbègbè kan. #EndSARS | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eledumare, o je o. """"""""@user: Ẹkú ojúmọ́ o. Ṣálàáfíà ni? Ṣe omi ò yalé o?"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹlòmíràn yan """"""""Orí"""""""" ẹran ìfẹ́ láti ọ̀run wá. Irú ẹni bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń máa ńsọ pé 'ó lẹ́ran ìfẹ́ lára"""""""". Ó nífẹ̀ẹ́ èèyàn, èèyàn nífẹ̀ẹ́ rẹ. #Ife | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹni tó fúsáárí kí ló ṣe idahungt olo iyagbe abi se igbonse | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹkún. Ẹ̀jẹ̀. Ìbànújẹ́. #BringBackOurGirls | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbogbo ọmọ #Nigeria, a kú òní o. A kú ọjọ́ òmìnira, ó di Àádọ́ta ọdún ó lé mẹ́ta . Àlàáfíà ni fún orílẹ̀ èdèe wa #Independence | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ALÁÀFIN AÓLẸ̀ (ÀRÓGANGAN) Lẹ́hìn tí Aláàfin Abíọ́dún wàjà, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ kò jẹ ọba. Ará rẹ̀, Aólẹ̀, ló gun orí ìtẹ́. Ìgbà Ọba Aólẹ̀ kìí se ìgbà tí ó mú ìdẹra wá fún àwọn ará ìlú. Ìwà ìninilára, aburú, Àrékérekè, ló gba ìgbà rẹ̀ kan. Gbogbo Ọ̀yọ́ https://t.co/xSC8MLBF8j | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Àjùmọ̀bí ò kan t'àánú; ẹni orí rán sí'ni ló ńṣe'ni lóore. / Blood ties do not guarantee merciful support; help comes o… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lágbájá npe Jésù. Tẹ̀mẹ̀dù npe Allah. Làkúsègbè npe Ọrúnmìlà. Bẹ́ẹ̀ ni ìwà ìbàjẹ́ ló wà lọ́wọ́ gbogbo wọn. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.