text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Kò sí ohun tí ẹ̀dá lè ṣe láì má fi ti ìṣẹ̀ṣẹ ṣe, ìṣẹ̀ṣẹ làgbà. Orí ìṣẹ̀ṣẹ ni ohun gbogbó dúró lé. #Iseseday #Iseselagba #Yoruba #August20 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
N kò le jókòó jẹ́ wo eré yìí nítorí pé òṣì ni wọ́n n ṣe | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user @user Dòdò díndín gbẹ nìyẹn now | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aláròyé: Ẹ ṣàlàyé nípa ara yín fáwọn tí kò mọ̀ yín Ọba Ògbóni Àgbáyé: orúkọ mi ni Dókítà John Dáìísí, èmi ni ọba Ògbóni Àgbáyé káàkiri gbogbo ilẹ̀ ayé pátápátá. #Ogboni | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé pé @user ti ṣe ìṣàmúdájú òdigì ọmọ Kwárà; ojúlówó ọmọ #Nigeria @user? Ó da bẹ́ẹ̀. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♪ Ọmọ #Yoruba ni mí o! ♪ #tweetYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ahhhakowekowuratoomogba tiyintemii yio bawa layeninu ola pelu ideraiku re wa betearun ko ni se wa ti | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo kí olówó ayé. Ẹ̀yin oní bùjẹ-bùdànù. Mo kí tálíkà gbogbo. Ẹ kú gáàrí múmu. Ẹ rọ́jú fi kúlí-kúlí dárà sí i kí ẹ tó gbé e mu. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
itura ti ode ba nijeria bayi ki eledua se ni aseyori awon oludeno alakatakiti ki eledua ba wa fi wan bu alo wan ni kari ki ama ri abo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user àwọn ògbójú ọdẹ ní í lo egbé láti gbé wọn kúrò nínú ewu láginjù. Bí a bá jẹ èèwọ̀, egbé lè gbé 'ni jù sọnù. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eyin eyan wa ekaaro eyin omo orilede naijiria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bótilẹ̀jẹ́wípé wọ́n ní èrò rere lọ́kàn, eré Nòfẹ́mbà Dúdú yìí yóò gbégbá orókè tí wọ́n bá ń ka àwọn eré tí kò ní láárí Kankan fún ọdún yìí. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
odò ìyá òò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Mo ti ṣe àtúnṣe, ẹ ṣeun fún àkíyèsí. Àṣìtẹ̀ ni. #EyoOrisa #EyoFestival #Lagosat50 #Egungun #Yoruba… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bíbọ́ láti abala kan sì ìkejì nínú sinimá yìí kò tilẹ̀ bójúmu rárá, bí wọn ṣe túmọ̀ eré yìí burú jáì, ìtàn ọ̀hún kàn fọ́n kálẹ̀ ni. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
òrìṣà oko or oṣó | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user A kì í dúpẹ́ ara ẹni ☺️☺️ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Dada awuru yale, yagi oko Olowo eyo, gbongbo ni ahoro Asiso o lara Otosi o niyekan Dada ogbegun, irunmangala Eran gbigbe o nijanja Aladeleye, abisu jooko Dada ogbegun Mo rade yo obinrin Gbon ori ade Gbo ori esu siwaju Dada ogbegun Gbo ori oro sodo mi | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user a ku oju mo. Oni a san wa sowo, san wa somo ati aiku ti n se baale oro. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọdún tuntun dé, Yáhrọ́bì mo bẹ̀ ọ́ o, ẹkún à sun rìn ma mà gbe bámi o. Ọ̀rọ̀ bí àdanwò, ma mà gbe bámi o."""""""" #OdunTuntun #2014 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àmọ́ nílẹ̀ẹ Yoòbáa wa níbí, kí á tó yá ọ̀rọ̀ lò, #OjoIsinmi ni ọjọ́ tí Ọ̀rúnmìlà Baba Àgbọnnìrègún sin Imi. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹkú ọjó ìbí @user . My secret crush on this app. Igba odún iṣẹju kán ní. Àṣèyí ṣàmódún. 🥂🥂🥂🥂🥂🥂🥂🥂 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ká rí 'ni lóde, ò dàbíi ká bá' ni délé. #Owe #Yoruba https://t.co/veSZ5CoY6Z | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi tí ẹran ìgbẹ́ fi ṣe ilé ti di ọgbà àwọn iléeṣẹ́ ńláńlá. Ariwo ẹ̀rọ ràbàndẹ̀ iléeṣẹ́ ti já wọn láyà, wọ́n ti kú tán àwọn tí kò kú sá lọ sí ọ̀nà jínjìn. Níbo wá ni àwọn ẹran ìgbẹ́ wọ̀nyí ń sá lọ? #EranIgbe #Yoruba #AyipadaOjuOjo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
o le te obirin lorun | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
olúwa please better make pizza at home a ò ní dààmú | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èwo nínú gbólóhùn wọ̀nyí ló ní fáwẹ̀lì aránmúpè? A) Fọn B) Fún D) Fín #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òpómúléró mọja àlekàn abímbéṣúàlé ọ̀yun mara ire tí í lo aṣọ kẹ̀ẹ̀kẹ́ ta dídùn aṣọ lèdìdì ènìyàn ọmọ òpó kiribí | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Egbe ori yin soke eyin ilekun ayeraye, ki a gbe yin soke ki OBA to po ni ipa ati agbara, ogo, anu,ibukun ati oreofe wole wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ojúmọ́ 're. A kú àyájọ́ Àádọ́ta ọdún ó lé mẹ́ta ta gba òmìnira. Àlàáfíà ni fún orílẹ̀ èdèe wa @user #Independence | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ayo ni Temi lojo gbogbo. Mo le ibanuje danu. Ope ni fun eledumare ! #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹmọ́ jíire lópòó'lé, àfèèbòjò jíire ní'sà rẹ̀. Emi náà ti jíire lónìí o. Mojúbà Olódùmarè. #ekaaro ooooooo. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oni lo'jo ibi mi... E bami dupe lowo Olorun fun aabo emi. @user @user @user @user http://t.co/l7tvIR0lU8 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user A ò kàn fẹ́ gbọ́ òótọ́ ọ̀rọ̀ ni. Kìí ṣe òṣèlú nìkan ni, bí kìí ṣe àwá ọmọ ìlú gan-an! Òwú tí baba gbọ̀n ni ọmọ nhun. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbogbo ìlú ilẹ̀ Yoòbá kọ́ ní kó ẹrú, #Ijebu, Èkìtì a máa mú ìlú mìíràn mọ́ ti rẹ̀ lẹ́yìn ogun. #OgunIleYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ojo ti iwa jegudu-jera ati Iwa eyii'okanmi ba kase'nle RT @user: Ọjọ́ wo ni ètò ìlera tó péye máa to wà ní #Nig ... | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ òtòlò kì í ya ìrá, ọmọ tí ẹkùn bá bí, ẹkùn ni yóò jọ. #EsinOro #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo kí dede ọmọ Ẹ̀gbá mọlíṣàbí #Abeokuta #Ogun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àdàbà kan ló p'ògèdè bíi p'ẹ́yẹ́lé ò gbó, ni gbegede bá gb'iná ní gbàgede àwon bánkì Màrínà o. Èèyàn ò sì ní fa gbùrù tán kíó wá so wípé òun ò ní fa'gbó. Òrò náà ń rúgbó bọ̀ o. #BankWars #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìbàjẹ́ ọjọ́ kan kì í tán lógún ọdún an indiscretion of one day does not get forgotten in twenty years acting in | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ajé olókùn ajé onírè ajé ṣálúgà gbé ire owó tútù tí ń dóṣìpaàgbàànà kò mí bùn mí níre owó tabua nítorí owó ló dùn ún jayé láìsí owó kò sí ènìyàn | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpìlẹ̀ Chief Daddy kíní ò dáa, ṣùgbón àwọn ẹ̀rín kan kò | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Yoòbá sọ̀rọ̀, ó ní 'yinni yinni kẹ́ni ṣè'míì' Bàbá tí ńgbé 'bi gíga mo fiìyìn fún o, torípé Ìwọ jí mi. Máa á ṣọ́mi bí ńṣe ńwá oúnjẹ oòjọ́ lọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orúkọ ń ro'ni, àpèjá a sì yẹ èèyàn. Orúkọ lo ro Ọlá-jùmọ̀-kẹ́ ti gbogbo ayé fi ń jùmọ̀ fi ọlá kẹ́ ẹ. #OniburediAna | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Olúwa ló kúkú ń ṣọ́ wa o... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí ìyàtọ̀ ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà ọ̀mìnì àti páráǹtà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ó jẹ́ ọ̀nà tó dára àmọ́ kò ní tumọ̀ - wíwá owó kíá kíá | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
àkàlà ò ní ṣaláì lo ẹgbẹ̀rún ọdún àwòkóṣe rere lẹ jẹ́ fún irú wa ẹ kú àyájọ́ ọjọ́ ònìí o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ rọra ṣe o. Pípẹ́ ní í pẹ́, akólòlò á pe baba. #ogbon #yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó dìgbà tí a bá sọnù, kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí í wá ara wa rí - Henry David Thoreau #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/L9GfkQGhq6 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Aami idani mo tuntun? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Lara awon ohun ti mo mu bo lati #akefestival ni iwe Ake ni Igba Ewe ti Wole Soyinka ko ti Akinwumi Isola tumo si ede Y… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀jọ̀gbọ́n wọlé ṣóyínká gba àmì ẹ̀yẹ òǹkọ̀wée lítíréṣọ̀ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Guynman yàtò. Ó yàtọ̀ pẹ̀lú u òsì | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ijoba apapo fg ngbero isuna ntn fun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iya ti je omo oodua awa yoruba omo kaaro o ji ire bi janduku olosha oga awon oogun oloro cocaine ni asofin ni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ ò mọ́? Ó da, òhun rèé >>>>>> #IpinnuOdunTuntun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ese, onise yin ti je o #IdanOriPapa #BarcaFC #ManCity #UEFA | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user se ori paper ni ati ma wa ma ra epo bayi? Ojojumo ni 'NNPC RELEASES TRUCKS' ofo lo bade ni ile epo. https://t.co/UxRMsel4l4 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ga; ọmọ #Yoruba ní #Ghana mo kíi yín o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàdógún ni ẹ̀sín Ọ̀rẹ́ èké Oṣù mẹ́ta tó k'ámọ̀ Ọ̀rẹ́ tíó ṣeni lóore Òjò a pa Bàtàá, a pa Janwonjawon!!! #ẸwàÈdè #YORÙBÁ https://t.co/ihxujoayeN | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ní kí wọ́n ó lọ ṣe ohun tí wọ́n bá fẹ́ ṣe ẹ ń dúró dè wọ́n họ́wù àgbà kì í ṣorò bí èwe è | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Like Yoruba people will say, ko seni tio wulo ninu gbogbo eyan tolorun da. Eni t'arope ko wulo, a se toka si f'eni tan foro bo.#Yoruba #PositiveVibesOnly | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Ẹ kilọ fun google koma yimi lohun pada mọ o. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo kàwé àgbẹ̀ sì ni mí ìwé tí mo kà ò díṣẹ́ oúnjẹ lọ́wọ́ mò ń ran orílẹ̀èdè mi lọ́wọ́ ni ìwọ náà darapọ̀ mọ́ wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3] A ò mọlẹ̀ t'ó lè mọ́ lọ́la, àfàìlà ọlọ́jọ́, bọ́jọ́ bálà à á lówó, à á láya rere, à á bímọ rere, à á kọ́lé, à á f'ọ̀kọ ṣẹsẹ̀ rìn. #Abameta | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Amin o. Awa naa a ma ri yin ba""""""""@user: Ẹ ká alẹ́ o. A ò ní ráburú lọ́dún tuntun o.""""""""""""""""amii | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eku owuro o ona wa ala loni o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àṣà wa l'ó ti wá di gbàtuẹ̀yọ̀. Ó ṣe! #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ọ baba lóké ọpẹ́ ẹ jí jí re dànsákì rẹ̀ ò ọba ńlá | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
lekanremilekunamos happy birthday odidi omo ilaje lekan remilekun amos aka omodafidi yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni yoruba tv | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo fẹ́ ya àwọn àwòrán tó wuyì dáadáa fún gbígbékọ́ sára ògiri inú ilé mi. Bóyá tí ng bá lè yà wọ́n láti orí òkè kan ní ìlú Ìbàdàn/Abẹ́òkúta. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
EWÉ AKÒKO Èwe Akòko ni ewé tí a fi ń j'oyè ní ilẹ̀ Yorùbá. Newbouldia Leavis is a leaf that, they use in coronating people in Yorùbá land. https://t.co/h2VxCpCkY9 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
nígbàa ayẹyẹ ṣíṣe tàbí òde aṣọ tí ọmọlẹ́gbẹ́ ń wọ̀ ni aṣọ ẹgbẹ́jọdá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ a n'ifẹ̀ ọmọlàkeji. Kí lo tu ń mu ayọ̀ ọkan wá jù ifẹ̀ lọ̀? #Happiness #HappinessDay | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iseju mewa ìsẹ́jú mélòó ló gbà kí ẹ̀bà tó tẹ̀ gaàrí ìjẹ̀bú ni o | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Korọrun lati wo | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ìrẹ́pọ̀ ló dùn o olùkù mi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aláwùràbí a dúpẹ́ nítorí i kíni nítorí a lajú ojú là a gbéra lórí ìtẹ́ ara ṣẹ gírí ara dìde ìdí abájọ rèé táa njúbà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àrán ni ti ifá ìgbìn ni ti ọ̀bàtálá ni ti ògún | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: Takada mi ati kalamu mi ise ya... RT @user: Àsìkò #Ibeere ti tó wàyí @user"""" :) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀rọ̀ yíndan-n-dé ni ọ̀rọ̀ t'ó ní ju ìtumọ̀ kan lọ fún àpẹẹrẹ retí tumọ̀ sí; rin etí, ìfojúsọ́ná. Sọ ìtumọ̀ j'ètè. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ògúnnágbòngbò ni àwọn yorùbá ń pè é àyálòèdè ni áálọ́ọ̀mù ni wọ́n fi máa ń ní pé ògúnnágbòngbò tí í dátọ́ lẹ́nu ìgbín | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí ló tún yẹ aláṣẹ ju ọpẹ́ bàntà banta lọ mṣe bí òun ló pa wá mọ́ láti ọjọ́ kìínní oṣùu ṣẹrẹ di òórọ́ òní ọjọ́ kìínní oṣù ọ̀pẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ta lẹni tó kọ ìwé Aláwíyé? A) J. F Ọdúnjọ B) D. O Fágúnwà D). Adébáyọ̀ Fálétí #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Can anyone double check the tone markings on the following please? Thanks! : Bí ilẹ̀ ńgbe òṣìkà, tí ikú ńpa olóòtọ́, bó pé títí, oore á máa sú ni ṣe #Yorùbá #Yorùbáproverb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtesíwájú ète wọn ni a fi dá ilé-iṣẹ́ West African Company Limited, Company of African Merchants sí èbúté odò Ọya ní 1863. #Nigbatiwonde | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#NigeriaCentenaryLotto àbí kí ni mo gbọ́ yìí? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#SickleCellAwareness in #Yoruba EJE Eje ni nkan pupa to n san ni ago ara wa Blood is the red fluid that flows in our body A ni ohun merin ninu eje 1 Padi eje pupa 2 Padi eje funfun 3 Padi eje platelet 4 Omi plasma There are four components of blood../1 #SickleCell #September https://t.co/qOjQQjiDNK | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó ní òun àt'ọkọ-àfẹ́sọ́nà òun láwọn jọ ńlọ, àmọ́ òun kò rọ́kọ òun, òun mọ ibi tó sa gbà, ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ sì wá ń'nú àpò tí wọ́n gbà #Oshodi | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ bá ni sọ fún àti àwọn agbátẹrùu rẹ̀ pé ayé kì í ṣe tẹnìkan ìgbà kì í ṣe tèèyà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fi yáná fún nígbà tí aláàfin àjàká rí àrokò náà ó pe atúmọ̀ rẹ̀ ọ̀sá kí ó sọ ǹkan tí ó túnmọ̀ sí fún òhun ọ̀sá ní wípé àwọn ará ifẹ̀ kò fẹ́ sangbà mọ̀ọ́ fún ọ̀yọ́ ni àti wípé alágbára ńlá èṣù kan wà lẹ́yìn wọn | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ilẹ̀ yìí ni wọ́n ti kó obì tí john pemberton fi ṣe ẹlẹ́rìndòdò coke cocacola àkọ́kọ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Ẹ ẹ̀ mà ní bínú ni o :) b'áwa ti nsọ ọ́ nílù u wa nùu :)) Ẹṣeun modúpẹ́. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọ̀n ni ẹ yẹ̀ wò, ọjọ́ ń lọ #idanoripapa #NGAvsFRA | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Wọ́n ní ẹni bá mọn'nú rò, á m'ọpẹ́ dá. Ló díá f'Álákọ̀wé Yoòbá lọ́jọ́ òní tó fi f'ọpẹ́ f'Ólódùmarè Ọba. #OlorunSeun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bàbá mo fẹ́ lọ sùn o ṣé ẹ yànda mi | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
agbe bó o délé kí o kí aró àlùkò bí o dọ́run o kí osùn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ORAL POETRY AND THE PLACES WHERE THEY ARE PRACTICED / EWÌ ALOHÙN ÀTI ÀWỌN IBI TÍ A TI Ń LÒ WỌ̀Ọ́N (1): The table below gives an insight on them and, the people that are allowed to take part in them. Àtẹ ìsàlẹ̀ yìí fi àwọn tí wọ́n ń kópa nínú àwọn ewì yìí hàn. https://t.co/KH4qqofUqh | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mò ń jáde lọ máa bá mi lọ̀ olódùmarè baba mi a dàgbàdàgbà má pààrọ̀ oyè pa àlọ àti àbọ̀ mi mọ́ kí n má bà á bìlísì pàdé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.