text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Òládùn àmọ́….. . . . Àsọdùn pọ̀ nínú eré náà. Ṣùgbọ́n mo gbádùn rẹ̀. Lọ́nà míràn ẹ̀wẹ̀, eléyìí wá láti gbóríyìn fà wọn dókítà àti elétò ara tí wọn kọjú àwọn àarùn káàkiri àgbáyé. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
a fola ailopin fun olodumare wo ologo meta sugbon okan soso bo ti ju imo wa lo ni a o ma figbagbo yin o amin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aalafia fun yin aláfíà ni o olúwa ṣeun o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé ìlú oní iyanrìn lẹ́búlẹ́bú ni ìgboro Ọ̀FÀ, ni a fi ń pe àwọn ọmọ bíbí ibẹ̀ ní Ọ̀yẹ̀rú/Yẹ̀rú (Ọ̀yẹ̀)? Ya… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àlàáfíà bá mi ṣe. Ajé bá mi ṣe. Ire gbogbo wá bá mi ṣe, ìyẹn lọ́jọ́ òní àti nígbà gbogbo títí láéláé. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Èmi náà lè gbìyànjú ....as pọ́pẹ́ oò mọ pọọ̀pẹ ò ní'bòji! Ìgbà tí gbangba tó wá ń dẹkùn kedere Tọ́mọdé tàgbà wá ń jẹ dodo orin wa💃💃💃💃 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ja mi si. RT @user: Àkànlò èdè ni """"""""gbé ... http://t.co/p1gvVPPuf5 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó já ni kulẹ̀ gan ohun tí a yọ láti Ìwé ìtàn ńlá a Half of a Yellow Sun | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
2/2 » Mẹ́ta là á pa á. Mẹ́ta là á mọ̀ ọ́n. Ọmọ láílo. Kí ni o? @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ìbẹ̀rẹ̀ orí fífọ́, ni ka ma ṣẹ orí mọ́ ògiri. Bí èèyàn bá sì wo ariwo ọjà, ó ṣeé ṣe, kí Olúwa rẹ̀, má mọ ohun tí ó ń ṣe. You haven't allowed the hype sway you away from your mission. Do you have any work you hope to publish soon? If any, what's the title? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ká róṣọ mọ́dìí; k'á ródìí mọ̀ṣọ, k'ára máà ti ṣe ìhòòhò. #Owe #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹ jẹ́ kí a fún àwọn obìnrin láàyè, àwọn náà ní ọpọlọ bí i ọkùnrin, eegun mẹ́sàn-án l'ọkùnrin ní, méje ni ti obìnrin, ṣe bí… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ojumo ire lo mowa loni ooº°˚ ire guusu ire ariwa ire ilaoorun ati ire iwooorun yo tewa lowo aku ojum | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Agbalumo di suga omo oba lo fe mu. https://t.co/qV6G60Ooj0 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user A dúpẹ́ o. Ẹ ò bá ṣí fèrèsé yín sílẹ̀ ni. Kí atẹ́gùn máa gba'bẹ̀ wọlé. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ope ni fun eleduwa oba ajiki ajige oba toju oba aye lo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bí èèyàn bá kú | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èèyàn dúdú ò lè bọ́ síta gbangba láti sọ pé ẹni báyìí lòun ní ìlú tí àwọn bàbáa rẹ̀ jìyà síṣẹ́ taratara fún | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ọjọ́ mẹ́ta o ìyáa wa @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀kọ́-Ilé jẹ́ ìṣọ̀rí kan gbòógì ni nínú ìwà àmúṣògo Yorùbá. Ọmọbìnrin tí ò lẹ́kọ̀ọ́ ilé ò le è tọ́ ọmọ tí yó ní ẹ̀kọ́-Ilé. #OjoOmobirin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kìí ṣe pé ó burú bẹ́ẹ̀ náà ṣùgbọ́n ìṣọwọ́ kọ eré àti ìdarí rẹ̀ ni kò ní àbójútó tí ó péye | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Eta @user Nínú àwa ẹ̀dá, ó ní ẹranko kan tí máa ń sùn jù lọ, ta ń mọ̀ ọ́ o? #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni ẹlẹ́dàá ọmọ titun ò fẹ́? Kí ni ọmọ titun kò gbọdọ̀ ṣe? #Esentaye #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: RT @user: @user @user @user Adie funfun ko mo ra re algba."""""""""""""""" Bo se wuni la nse Imale eni o! | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀ṣììrì meaning ► enemy àtiwájú àtẹ̀yìn ni ọ̀ṣììrì wà enemies are both in the front and in the back | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ta ló wà ń díẹ̀? #Oga nìkan ló mọ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ní òní ojórú òrò wa ò ní rújú, ayé wa ò ní dàrú, ilé wa ò ní dàrú """"""""Orí adìye kì í burú kí ó yé dúdú"""""""" Orí w ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ire-Elédùmarè, wà á ju olóókọ lọ láṣẹ Elédùmarè. A gbó, a tọ́, a ṣure. Tó! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ha ba wa laye lagbara olorun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user A kì í dúpẹ́ ara ẹni. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ní ọdúnun orílẹ̀èdèe ni ó ṣe ipò kẹ́rin orílẹ̀èdè tí ó ń ta èdìdì òdòdó sí òkè òkun jù lọ ️ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ojúmó ayò ló mó wa lónìí; Aò r'ógun ìbánújé; Ajínigbé kòní gbé wa; AJínigbé kòní gbé omo wa; Ohun ìjà òtá 'á... http://t.co/… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user Fún ọjọ́ méjì gbáko. Ọ̀la àti ọ̀tunla. Agbádá ni kí n wọ̀ ni àbí bùbá àti sọ́ọ́rọ́ :)""""Kò séyí tí ò wuyì :) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹni àìkú kì í kú a kú tì a ti gbé kú dè a ò kú mọ́ a kú ọjọ́ọ̀sẹ̀ o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní òye tèmi o. . Ìtàn bí èrè yìí ṣe lọ dùn gan-an ni mo sì fẹ́ràn ohun gbogbo nípa sinimá yìí | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ikọwẹ ti o yanilenu. . Dokita Lanre jẹ eré tó yanilenu. Mo gbádùn arami nigbati mo wo. O ṣàfihàn igbe-aye ojojumọ awon eniyan, iye-eniyan ati ẹkùn, o yàtọ o sí dun fún wíwò. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
omoomo re dokita adadevoh lo gba ile wa kuro lowo arun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♫ Nàìjíríà yìí ti gbogbo wa ni, kò máà gbọ́dọ̀ bàjẹ́. Torí kò síbòmìíràn tí a lè lọ, àjò ò lè dà bíi ilé... ♫ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
B'ó ṣe wà ní Òkò ló wà ní Aké, b'ó ṣe wà ní lìkì ló wà ní gbànja. Kíni gbànja? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 5. Ní ilẹ̀ẹ Yorùbá, ẹnìkan ṣoṣo ni kì í dọ̀bálẹ̀ fún ọba aláṣẹ igbá-kejì òrìṣà, ta ni ẹni náà? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Bí ẹ̀mí bá gùn, báà kú, ire gbogbo ni í ṣé ojú ẹni. / If we can live long and not die, we will yet experience lots of… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òróró àràmàndà inúu rẹ̀ pàápàá wúlò fójú tójú yíò ma ríran kedere á tún máa mú ara dán bíi wúra. #Yoruba #asala | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Àààlò o! Òjò patapàtà, ó d'órí àpáta, ó rá. Kí ni o? Ẹsẹ̀ ẹṣin ni o! 🏇 *Bí ìróo bàtà ẹṣin-ín ṣe máa ń dún lórí àpáta, yóò… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
buoda oju re re o to ijo meta lohun orin sunny ade e kaaro oh ojumo ire oh rt ẹkú ojúmọ́ o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
n óò máa tú aṣọ lójú eégún ní ọjọ́ ẹtì o ṣeun àwé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù tó dára ni!. . Láì fa ọ̀rọ̀ gùn…Eré yìí dunni láti wò sùgbọ́n wọ́n sàlàyé rẹ̀ dáadáa pèlú ọgbọ́n. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Farming dá lé ìtàn ayé ò kọwé ati Olùdarí Adéwálé Akinnuoye-Agbaje gẹgẹ bí ọmọdé kùnrin Nàìjíríà, tí àwọn ẹbí alawọ funfun gba sí ọdọ ni ọdún 1980. Èyí jẹ òun tó ṣẹlẹ larin odun 1960 sí ọdún 1980, èyí tí a mọ̀ sí ògbìn. Fíìmù náà dá lórí bí ọmọdé kùnrin yìí ṣe da'mu láti mọ ẹni tí o jẹ,pẹlu ìyá alawọ funfun tí o jẹ ẹlẹ... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Àfẹ́ẹ̀rí kan ò ju k'á rí igbó ńlá kan bọ́ sí lọ; ẹbọ kan kò ju ọ̀pọ̀ ènìyàn lọ; """"""""Òrìṣá gbé mi lé àtète"""""""" kan ò ju orí ẹṣin lọ. #EsinOro🐎 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Erín kú mọ̀ngúdú fi jẹ, ẹfọ̀n ku mọ̀ngúdú fi jẹ, mọ̀ngúdú wá kú kò rí ẹni tí yóò jẹ òun. #yoruba #proverb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
10. 🏠 Igbó ìgunnu => ìgúnnukó Ìgbàlẹ̀ => egúngún Ilédì => ògbóni _____ => orò #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #Language | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user I would call it """"""""Èrò onírúurú ìhun tí ó mú ohun ṣiṣẹ́ bí ó ti ṣe yẹ"""""""", nítorí bí a bá tú u palẹ̀, ìtúmọ̀ structure/structural ni ìpìlẹ̀/ìgbékalẹ̀/ètò nǹkan tí a fi hun kínní náà papọ̀ tí ó fi di ọ̀kan. Èrò/ìgbàgbọ́/òye sì ni a lè lò fún theory. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
omoluabi osinbajo ìwọoòrùn guusu orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni a ti bíi ní ifowosowopo pẹ̀lú ààrẹ muhammadu | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó túni lára ó sì tún dání lára yá, Fíìmù ‘TA A L’ọ̀gá?’ jẹ́ ìkan lára àwọn fíìmù tí Nọ́líwuùdù yóò fún yín tí yóò mú ayọ̀ bá ọkàn yín nítorí ó fi hàn láìsí àní-àní pé àwọn ènìyàn Nàìjíríà ní ọpọlọ àti ẹ̀bùn fíìmù ṣíṣe tí ó pọ̀ gan-an. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Èyí ni àkọ́kọ́ nínú ìròyìn oníṣísẹ̀ntẹ̀lé ẹlẹ́ka-méjì tí ó dá fìrìgbagbòó lóríi ọ̀rọ̀ ìkórìíra ẹni, ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ àti irọ́ lórí ayélujára ní Nàìjíríà lásìkò ìbò ọdún-un 2019. https://t.co/GVcg9TQVJU | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eda to mose okunkun, ko'dakun mama d'osupa Loro. #Yoruba #Language #Nigeria #Africa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹnu lẹbọ, ahọ́n ẹnu ń mú ni í là, òun náà ní í kó bá ni. Ẹ wòreré ayé kí ẹ ríi b'ẹ́nu ti í pa ni. #Enulebo #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ayọ̀, ire àti àláfíà ọ̀hún á káárí gbogbo wa o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 9. Ọọ̀ni ti Ifẹ̀, Àkárìgbò ti Rẹ́mọ, Ataọjà Òṣogbo. Aláàfin ti Ọ̀yọ́, ____ ti Èkó. #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user wọ́n á jẹun ọmọ pẹ́ pẹ́ pẹ́ láyé. Yèyé abiamọ tòótọ́. #EkuOjoIbi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹja tí a fi ìwọ̀ mú, ló jẹ́ kí gbajúmọ̀ ọ́ jẹ èkòló. The fish, caught with the fish-hook (typically using earthworm a… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìsejáde ti wà ní gbogbo ibí, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun kíkọ́ kò ní ìdàgbàsókè ní kíkún. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Eré nlá làti ọwọ́ọ Nollywood. . . . Wọn ò kọ̀ kọ erée Lion Heart lásán. ó fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun tí on ṣẹlẹ̀ ní Nàíjírìa hán ni gbàgede ti o ma gba eni tí ó bá farabalẹ́ tí ósì ní ojú inú láti rii ninu eré naa. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Ire àìkú tí í ṣe báálẹ̀ ọrọ̀..... #Aṣe #Atelewo #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÀLỌ́ ÀPA-GBÈ: Àlọ́ àpa-gbè jẹ́ àlọ́ tí ó ní ìtàn àti orin nínú. Ẹni tí ń pa àlọ́, á ma sọ ìtàn. Ṣùgbọ́n, tí ó bá dé ibi orin, Ẹni/àwọn tí wọ́n ń pa àlọ́ fún, á ma gbe orin. Fún òye ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, ẹ fi fídíò yìí ṣe atọ́nisọ́nà https://t.co/EkDvYurt10 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi orí dá ni sí là á gbé #Nigeria | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
egun ni fun omo ti oba tu ihoho iya re nita gbangba ode pa iya re lekun nitori alakori jonathanu | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
túmọ̀ gbólóhùn yìí sí èdè yorùbá ► jide im so sure youve sworn not to visit my house | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A ti ngbàdúrà fún ọdún méjìléláàádọ́ta báyìí. Ọdún kíní ni Ọlọ́run ti dáhùn àdúrà. Eti wa ló di. #NigeriaAt52 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtaàdógún : ẹ̀ta dín ní ogún ➡️ 20 minus 3/space of seventeen days (rí mi ní ìtaàdógún ⏩ see me in seventeen days) #InYoruba #learnyoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀sìn ò gbọdọ̀ fàjà ọmọ #Naija. Bí èdè lẹ̀sìn rí, sọ tì ẹ kí n wí tèmi. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Okookan laa ji kasuunre o """"""""@user: Kasun Layo, O di Ola ki Ile To Mo..... Ao Ni Ti Oju Orun Doju ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Shangba fo! Ogun Idile ni Ile Yoruba! Ewo bi Oba Rilwan Akiolu se wuwa bi omo odun mejo, ni waku Ooni ile Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi. https://t.co/2iaAwPyW3F | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Obama mọ ọ̀rọ̀ ọ́ sọ kí orí ènìyàn wú, ọ̀gá ńlá sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ ni. O ti ṣe ìwọ̀n tí o lè ṣe, ó ti wọ àkọsílẹ̀. Ó dìgbòóṣe! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Omo dudu ile komobe se njosi,pupa tomo be se okuku sinle,Omo moreye mamaroko, morokotan eye matilo,Omo moni isunle mamalob… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní ìparí, ẹ jẹ́ kí á yàgò fún ìwà ìyẹpẹrẹ nǹkan ìní àtilẹ̀bá a wa, bí a óò bá pààrọ̀ àwọn gbólóhùn òwe àti àwọn ewì alohùn bẹ́ẹ̀ sí tiwa gẹ́gẹ́ bí àyè ṣe fi gbà nínú ìmọ̀ ẹ̀dá èdè àti ẹ̀kọ́ èdè, á dára kí a gbé ìlò àti èrò wa lórí ìwọ̀n kí a tó pinnu àtiṣe. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé """"""""iṣú wà"""""""" ni ìtumọ̀ Èrúwà? #Oyo #Yoruba https://t.co/wyeTwVZwqL | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ́ ká ṣe pẹ̀lẹ́ nínú oṣù Agẹmọ yìí ó. A kò ní sìṣe láṣẹ Èdùmàrè🙏 YouTube:@user #oweyoruba #yorubaproverb #EdeYorubaRewa #yorubadun #yorubanimi #yorubatradition #yorubahood #yoruba #yorubademon #Alagemo https://t.co/txjGoX22yG | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user pátákò ẹṣin ni oooooooo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo gbé Àríwá lárugẹ . . . . Fíìmù yìí ṣe àfihàn àwọn ẹ̀yà ẹlẹ́wà ti Àríwá Nàìjíríà pàápàá jù lọ ìpínlẹ̀Bauchi. Nkò le dúró láti bẹ àwọn ọ̀rẹ́ mi wò. O ṣeun fún sísọ ìtàn ẹlẹ́wà kan! | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
folu aku ìgbélé yi o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù yìí ni àdó olóró náà. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
piri lo olongo ji ojumo ire lo mo wa loni rt a kìí bá olókùnrùn ẹyẹ kankan lórí ìtẹ́ ẹ ṣara gírí ẹ dìde | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user àṣẹ ire! Ewu ńlá ni o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user @user Ė şé o, Komíşómà wa! Kí àwa omo Òduà jákèjádò àgbáyé gbìyànjú làti tùnbò gbè èdè, às… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
🇳🇬(#Yoruba) Nipa aabo ailewu ti awọn kokoro ti o le jẹun, titi di bayi a ko ti ri boya #Salmonella spp tabi #Listeria_monocytogenes ati awọn kii kekere ti #E_coli. (itumọ nipa Google tumọ si, laisi ẹri). | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Lori Afefe #KonkoBelow latowo @user lori eto #LawujoAriya pelu @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọ́n á ní kí ló pa á kò kú sí hun tún ń pa ni lẹ́hìn ikú sábàbí ló yàtọ̀ọ̀tọ̀ ẹni ire nikú ń mú lọ aṣebi ń kọ́ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Odun yi atura, koni le koko mo mi(2X), ohun ti mo da'wole a yo ri, ohun ti mo bere l'Oluwa yo se fun mi, Odun yi atura, koni l ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Afẹ́rẹ́ òwúrọ̀ yìí tutù yàtọ̀, ìrì sẹ̀ lóru mọ́jú. Ẹ kú ojúmọ́ o! 🙌 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ gbọ́ àriyànjiyàn ìlera ààrẹ nílé ọtí. Àwọn kan fẹ́ kí Buhari kú. Ọmọ Nàìjá kí ló dé! 😦 https://t.co/vYK0WVH2pZ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré tó n duni nínú ju eré àláwàdà lọ, Lionheart ti fi ààmì hàn wípé fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kàn àpéjọ àgbáyé ní ọ̀nà nlá | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọ̀gá fi ọgbọ́n àrékérekè ọwọ́ wọn ba ti wa jẹ́, àmọ́ kò yé ọ̀pọ̀lọpọ̀ wa bẹ́ẹ̀ ẹni ire la pè wọ́n, ẹni ègbé ẹni ẹ̀tàn ni wọ́n. #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ORI KERINDINLOGOJI: ÈTÓ ÌGBÓTENU ENI KI ATO DÁJÓ (GBO TI IDA KEJI) #Law2go #HumanRightsinNigeria #Section36 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... inú bí gómìnà Èkó, tí ó fi dí gbogbo ọ̀nà tí ó wọ Abẹ́òkúta láti Èkó ní 1863 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Orlando Owoh ni sir. Orlando Julius wa laaye """"""""@user: Olóògbé #OrlandoJulius kọrin, ó ní; """"""""ẹ ṣe rere yé o, ẹ ṣe rere k… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbọgbọọgbọ lọwọ́ọ́ yọọ́ Jorí; gbọgbọọgbọ ni màrìwò ọ̀pẹ̀ẹ́ yọọ́ jọ̀pẹ̀; gbọgbọọgbọ ni ẹ̀ẹ́gun òkèèrèé yọọ́ jù wọ́n. N ó yọ jọ̀tá lọ. #Iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Jẹ kí n jẹ ní í mú ayò dùn. #EsinOro #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yèyé tí kì í fi ǹkan ṣòfò bẹ́ẹ̀ sì ni kì í da oúnjẹ nù | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òro ìwúrí opin ose .. #kaftantv #kaftantvyoruba #kaftan #yoruba #yorubaculture #yorubanimi #yorubalanguage #instagram #africa #african #nigeria #lagos #ekiti #ondo #ogun #oyo #ibadan https://t.co/4IdxliXooI https://t.co/6Yx01FNaZw | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Ẹkáàárọ̀ o. Ati baba, ati ọmọ. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.