text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
eni ti a ko nika to gba oun to wa ninu e tele lo se
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Màgódò ❌ Máàgódó ✔️ Máà-gún-odó ni a sọ di MÁÀGÓDÓ. Máàgódó l'ó tọ̀nà ní pípè. Máà gún odó l'ó di MÁÀGÓDÓ, àṣìpè ni MÀGÓDÒ. #Oruko #Yoruba #Magodo #Lagos
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a kò lè tìtorí pé a fẹ́ kí ẹṣin kú iṣẹ́ ka wá ní kórí adé rinsẹ̀ we cannot ask the king to trek simply because
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé Adébáyọ̀ Ògúnlèsì ni ẹni tí ó ni pápákọ̀ òfuurufú #Gatwick nílùú London? #Yoruba https://t.co/VkOWSmi0RD
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user Oruko mi ni Ojewale Temitope abi mi si ilu Modakeke, ibe na ni motigbe dagba. Emi ni omo won lakoraye omo akin loju Ogun #TweetinYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Báwo la ó ṣe dáwọn ọ̀darànmọràn yìí mọ̀? Àwòràn wọ̀nyí kéré, kò rí kedere tó.""""""""""""""""@user: https://t.co/g9Jq82OsU5… https://t.co/9I6oebe3ET""""""""""""""""
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user E ku #TweetinYoruba day, mo ri pe ojogbo ni yin ni ede yoruba, awon still learn lowo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yùsúfù Ọlátúnjí ló mìgboro tìtì ní 1960 sí 1970. Wọ́n ní “àgbà ò sí nílùú, ìlú bàjẹ́; baálé ilé kú, ilé di ahoro. #Sakara #Orin #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a ò rọ́jọ́ so lókùn a ó kí ara wa káàárọ̀ láàárọ̀ ọ̀la lọ́lá olúwa ódàárọ̀ o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ kú ọ̀rọ̀.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀rù bà á, kò le è gbé ọmọ titun padà síletò ni ó bá gbé e jù sílẹ̀ nínú igbó. #ItanObaIgala #Yoruba #Kogi #Igala
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÌṢẸ̀DÁLẸ̀ ÌLÚ ILÉṢÀ Gẹ́gẹ́ bíi ìtàn àtẹnudẹ́nu Iléṣà, ọmọba Ifẹ̀, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ajíbógun (tí a sì mọ̀ sí Òbòkun), ni ó tẹ Iléṣà dòó. Nígbà tí ojú ń yọ Odùduwà lẹ́nu, Ifá ní kí wọ́n wá omi òkun wá. Ajíbógun ló fi ara rẹ̀ sílẹ̀, láti fi omi òkun náà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọjọ́ àìkú ni a tó ó wú ọkùnrin nì jáde padà láti inú sáà ilẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user A kìí dúpẹ́ ara ẹni o. Ẹṣeun, mo ṣ'àmí ẹ̀.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò dára
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ọmọdé gbọ́n àgbà gbọ́n la fi dá'lẹ̀ Ifẹ̀. Ẹ bá mi rán wọ́n létí. @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọ̀rẹ́ mẹta ni ìyà ń jẹ, kódà ó ti sọ wọ́n di pákò. Wọ́n pa ìmò pọ̀ láti wá ọ̀nà àtilà. Wọ́n ń wá Àṣírí Ajé. Ǹjẹ́ àbùjá wà lọ́rùn ọ̀pẹ? Ǹjẹ́ àṣírí ajé wà? Kíni ìgbẹ̀yìn àwọn tí ń kánjú wá owó? #AsiriAje #Atelewo #YorubaBooks #Yoruba https://t.co/hE72UVFxsp
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ka sise bi eru ko da nkan Oluwa nikan lo le gbeni ga""""""""@user: Kìràkìtà ò dọlà......RT""""""""@user: Ile aye yii o gba giragira""""""""""""""""
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Inú kan la fi gbà wọ́n, ète àti èrò wọn ni a ò mọ́. Aṣọ wa ò b'ójú mu l'ójú wọn, wọ́n gba ti ọwọ́ wa, a gba ti ọwọ́ọ wọn. #Nigbatiwonde
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Àlàáfíà ni o, a dúpẹ́. Inú ẹni kì í dùn ká pa á mọ́ra, ìdùnnú á ṣubú l'ayọ̀ wa😊😊😊
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ta l'ó dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ èèbó nínú àwòrán yìí? #Ibeere #Yoruba https://t.co/HpEOkqcQGm
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ǹjẹ́ o lè kọ ìtàn ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, tàbí ní èdè Yorùbá? Ó sì lè jẹ́ ògbufọ̀ èdè láti Gẹ̀ẹ́sì sí èdè Yorùbá ni o lè ṣe, o jẹ́…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré tí kò ní ìdí
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ta ni yìí gan an bí ṣe ń pa ọkùnrin ló ń pa obìnrin bẹ́ẹ̀ ní í pa ọmọdé àgbàlagbà àmọ́ àwọn mẹ́kúnnù ló ń forí kó o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìlò ohùn àwọn òșèré mìíràn lórí tí àwọn tí à ń wò ní ọ̀nà tí kò dára rárá ní èyí àti ìṣọwọ́ ṣeré tí kò kún ojú òṣùwọ̀n dé orí pé kò dára rárá. Àlákálàá ni èyí yóò fún ọ
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Bí ọmọ yín bá darapọ̀ mọ́ wa, lẹ́yìn oṣù mẹ́ta, yíò le kà, kọ àti sọ èdè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ni yíò tún le kọ́ láti le kọ èdè Yor…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
BRINGING BACK THE CLASSICS /A MÚ ÀWỌN ORIN AYÉBÁYÉ PADÀ WÀÁ: We bring one of the most beautiful love songs of all time to you 💖 A mú ọ̀kan nínú àwọn orin ìfẹ́ aládùn wá sí etí ìgbọ̀ọ́ yín 💖 Eji Òwúrọ̀ - @user (2003) https://t.co/UUS9M4ZCpu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Odùduwà, Ooduwa, Odudua, Olofin Aye or Oòdua, is the ancestral dynasties of Yorubaland. Oduduwa represents omnipotency, the…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ma ń lò ó fi pa ọ̀rọ̀ jẹ àti láti fi rú aláìgbédè lójú. #Yorùbá #Animal #Metaphor
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user kun fun opolopo ope. Oku die ki @user da lagbo nu amo Iroko tiraka ninu idibo eni http://t.co/pPaepcsJiq
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Odùduwà, igbá ńlá méjì àdéìṣí. #Owe #Yoruba https://t.co/RJjKdtFLyI
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O lòdì si òfin ki ènìkéni fi o si inú ìjìyà tàbí íróra nipa kpe o se e ni ìsekúse. #Law2go #HumanRightsinNigeria #Section34 #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""""""""""Ori yen so @user: Ilé ayé, ilé asán. Gbókègbódò ni ilé ayé.""""""""""""""""
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣé pé a ò tó ti gbogbo àgbáíyé ṣe àbí òmìrán afíríkà mà ni wá d
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀ ẹ́ gbayì ní
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user @user A o gbero pe afe yan se lodi Ooooooo....Egbe awon Oludari ile epo (IPMAN) lo so - http://t.co…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ ṣeun. Kòsí ewu kankan ní Naija o :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé Ọ̀rúnmìlà bàbá Àgbọnìrègún ma ń ran gbogbo àgbáyé lọ́wọ́ lọ́jọ́ ayée ẹ̀. @user #tweetYoruba #Ifa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eemo l'Agege! Aafaa fi eyin adie ati iyo we fun Aanu, won lo fee fi soogun owo ni - Alaroye
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí eré bí àwàdà, èmi náà bá ṣe kòńgẹ́ òkúta kan tí ń tàn yirin-yirin. Mo yáa tètè kì í b'àpò o jàre. :) Orí mi sọre. http://t.co/epXb9AjuRn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìlànà bí wọ́n ṣe máa ń kọ́ ọ̀nà àbáwọlé jọ ti àwọn ará #Rome tí wọ́n ṣájú àwọn lárúbáwá ṣe àkóso #Spain. http://t.co/5T0NJtTlVx
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ t'ó ń wá onígbèsè t'ó jẹ bàbá rẹ̀ lówó, bí ò ṣọ́ra rẹ̀ á rí ẹni bàbá rẹ̀ jẹ lówó #Owe #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjímèrè fẹ́ràn láti ma ṣeré lórí igi. Kòkòrò Aládi ma ń wá lórí igi. Tí ìjímèrè bá gun igi tó ní kòkòrò Aládi lórí, ọwọ́ tí kòkòrò náà ma fi jẹ ẹ́, ìjímèrè náà á gbà, wípé, òhun si igi gùn.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹni tí a kò bá lù ní ìpèbí kò le è jẹ ọba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ Odùduwà dìde . bọ́'sípò ẹ̀tọ rẹ . ìwọ ni. Ìmọ́lẹ̀. Gbogbo Adúláwò . """"""""𝑅𝑖𝑠𝑒 𝑢𝑝 𝑐ℎ𝑖𝑙𝑑 𝑜𝑓 𝑂𝑑𝑢𝑎. 𝑇𝑎𝑘𝑒 𝑦𝑜𝑢𝑟 𝑟𝑖𝑔ℎ𝑡𝑓𝑢𝑙 𝑝𝑙𝑎𝑐𝑒. 𝑌𝑜𝑢 𝑎𝑟𝑒 𝑡ℎ𝑒 𝑙𝑖𝑔ℎ𝑡 𝑜𝑓 𝑡ℎ𝑒 𝑏𝑙𝑎𝑐𝑘 𝑤𝑜𝑟𝑙𝑑"""""""" This is my fav part of the #yoruba Anthem. https://t.co/wjm3QfDCjR
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
láti ṣètò èrò ọkàn èèyàn. ÀWỌN IGUN MẸ́RIN AIYÉ Bí babaláwo bá ń dífá, yóò pe àwọn agbára orígun mẹ́rin ojú ọpọ́n, nípa sísọ, """"""""Ìbà ṣẹ ní Ìlà-oòrùn Ìbà ṣẹ ní Ìwọ̀-Òòrùn Ìbà ṣẹ ní Gúúsù Ìbà ṣẹ ní Àríwá"""""""" Ìlà-Oòrùn wà ní òkè ọpọ́n Ifá, èyí tí ó dúró fún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aro tí tẹ̀gbọ́n-tàbúrò yìí wọ sẹ́sẹ̀ ni agbégẹ̀lẹ̀dẹ́ ń kó sẹ́sẹ̀ di ọ̀la. #Gelede #Yoruba #Ifa https://t.co/fBbRcezLXD
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Máà jẹ́ kí àgbàrá ìgbàlódé ó ṣàn ọ́ lọ. Máà sọ ilé nù. Máà gbàgbé orò ilé. Máà gbàgbé àṣà. Máà gbàgbé èdè. Rántí ọmọ ẹni tí ìwọ ń ṣe. #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aworan yoruba parapo ni ilu akure gomina ipinle ondo asiwaju bola tinubu ati amofin rotimi akeredolu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Aníbiírè kìí sòkò fún gbogbo ajá tó bá gbó lónà. 👊🏿 A few words for the year ahead. #subtitles #oroisiti #Yoruba #havea…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lọ́jọ́ kan, ajá àti ẹbíi rẹ̀ tí ó jẹ́ oníkòkó, fi ìlú wọn tẹ́lẹ̀ sílẹ̀, wọ́n sì kó wá sí ìlú àwọn ìjàpá, ìlúu Máṣeé. #Itanilumasee
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lálá tó re òkè, ilẹ̀ ló ń bọ̀. Ọlá èmi tìrẹ ò ní re ilẹ̀ láéláé lọ́lá Elédùmárè nítorí òkè l'ẹmu ń ru sí. #Yoruba #Owe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù tí wọ́n rí dárí dáadáa ni tí wón sì rí tò pọ̀. Ohun tó dálè lórí wọra dé lẹ̀. Wọ́n rí ìtàn yẹn sọ tí wọ́n sì rí ṣe pẹ̀lú àwọn òșèré tó yáyì
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àt'ẹni k'àwé, àt'ẹni kò kà t'ó bá ti jẹ́ ọ̀ṣọ́rọ́, ó yẹ kí I.T.F ràn án lọ́wọ́ """" #OhunOdoNigeriaKan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Layajo ojo oni ni odun 1999 ni oko ofurufu Egypt Air 990 ti o nlo si Cairo lati New York ja lule ni Nantucket, enia 217 ni won di ero orun
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ajé ò jẹ́ kí n ní ọ lọ́wọ́ kí n rí ọ lò rí ọ ná rí ọ fi ṣehun rere má jẹ̀ẹ́ kí n ní ọ lọ́rùn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ayùn ► a saw ayùn rẹ́ igi the saw sliced the tree àyun ► departure àyun mo rí a ò rábọ̀ saw departure not the return
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orúkọ mìíràn wo ni wọ́n tún ń pe ọ̀rúnmìlà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ògún gbọ́ t'aya rẹ̀, ó ṣe ọ̀kan fún un, ọ̀pá yìí wá á di méjì, Ọya nìkan, Ògún nìkan. #OsuOgun #Ifa #Yoruba #Ogun7
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nígbà tí òun kan ṣoṣo tí àwọn ènìyàn ń sọ dára dára nípa ère jẹ́ àwò, ó yẹ kí ènìyàn mọ̀ pé òun kò ní gbádùn ère náà.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
la ojú rẹ ṣàyẹ̀wò ara rẹ dénúdénú ǹjẹ́ ayé tí ò ń gbé tẹ́ ọ lọ́rùn bob marley
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Egbògi """"""""ayọ́bi"""""""" nìyí, ó dára kí aláboyún ó máa mu ú. Wẹ́rẹ́ l'ewé ń bọ́ lára igi, bẹ́ẹ̀ ni yóò rí bí ó bá d'ọjọ́ ìkúnlẹ̀, ìrọ̀rùn l'ó bá dé fún abaraméjì. Ewé ejìnrìn àti ọṣẹ dúdú ni a fi tò ó. #Yoruba https://t.co/pXk2SyhHeW
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Nitori na, ayarabiasa tun pelu gbgbo nkan ti a npe ni digital media a ti alagbeka.IAFEE
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oníko ń wọlé. #EyoOrisa #EyoFestival #Lagosat50 #Egungun https://t.co/zYZBb9cGtd
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹní màá máa ní èjì ireè mi yóò dèjì ẹ̀ta irúgbìnìn mi yó ta ẹ̀rin ẹkúnun mi yóò dẹ̀rín àrún mi ò ní kú mi ò ní rùn ẹ̀fà n ò ní á tì
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lionheart jẹ́ fíìmù tí o lágbára tó sì fi ìbálòpọ̀ hàn dáradára ní ibi-iṣẹ́ mi orílè-èdè Nàìjíríà. Ó wá ní ọ̀nà òtítọ́, àsọtẹ́lẹ̀ gíga àti ní ìtọ́sọ́nà ní ye aláìlágbára nípasẹ̀ Genevieve Nnaji. Ṣùgbọ́n ní ọnà ìdákejì, iṣẹ́ ṣíṣe rẹ̀ kò jẹ lásán àti wípé o fi iṣẹ́ ìgbéga hàn fún òṣèré ati awọn òun èlò òṣèré. Fíìmù nà...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: 🎼🎵🎶 Ẹ máa pé kó ṣẹ. 💵💶💷💰 Owó á wá wa wálé 👶👶👶Ọmọ á wa wálé 🚗✈️🚤 Ire gbogbo á wá wa wálé #Iwure #OjoAje #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Sanyeri at iyawo re. Sokoto □ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #hausa #igbo #yoruba #oodua #oduduwa #ondo #oyo #lagos #kogi #edo #delta #ogun… https://t.co/oQRJaNYDAK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orúkọ ọmọ ẹranko wo ni ìwọ́ mọ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṢÍṢE IṢẸ́ PẸ̀LÚ ÒṢÌṢẸ́: ÀWỌN ONÍṢẸ́ ỌWỌ́ Àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ bíi, alágbẹ̀dẹ, àwọn tó ń rọ Idẹ, àwọn tó ń hun aṣọ, àwọn tó ń hun ẹní, àwọn agbẹ́gilére, àwọn ọ̀mọ̀lé, oníṣègùn abbl, ọmọ iṣẹ́ ni wọ́n fi ń gbéra níbi iṣẹ́ wọn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọjọ́ àbámẹ́ta tí ọjọ́ kérésì tẹ̀lé ẹ wá wo èrò lọ́jà ọjọ́ àwọn oníṣòwò lòní jẹ́ ajé ò lè ṣàì wọgbá dandan ni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹṣin tuntun, ọ̀nà tuntun, gèlè tuntun, ọmọge tuntun, owó titun, ilé tuntun, aya tuntun, ìlera tuntun."""" #Iwure#OdunTitun2018
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Irú Ọ̀yọ́ rè é o. #ounje #yoruba http://t.co/j9gnygvBvg
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ara mi le o piri lolongo nji aa ki bokunrun eiye lori ite
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nǹkan tó ṣe kókó láyé kìí ṣe pé a gbé'lé ayé. Ìyàtọ̀ tó lápẹ̀ẹrẹ̀ tí a ṣe láyée àwọn èèyàn láá t'ọ́ka ayé tí a darí"""" http://t.co/9g3Rl0agiD
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojútì gbáà. 'The Vendor' jẹ́ eré tó dá lé ìwa wòbìà àti ẹ̀bi.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
... Ẹ bò'díi yín o, ó ti sú wa á wò"""" ►► http://t.co/hUVQWrOcNi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àìsí níbẹ̀ láì bá wọn dá sí i. Àwa náà ńbẹ níbi Ayẹyẹ Àyájọ́ Èdè Abínibí Àgbáyé 2020 Àti Ayẹyẹ Àádọ́ta Ọdún Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Alagbara aye, e rora. Ohun gbogbo ni i bo wa tan. #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
swiftly) BÍ OÒ MỌ ERIN, OÒ GBÓHÙN ERIN? (if you don't recognize greatness, don't you see the signs)? IBI TÍ ERIN MÉJÌ BÁ TI JÀ, KORÍKO IBẸ̀ LÓ MA JÌYÀ RẸ̀ (powerful people fighting, leaves long lasting negative effects on the people around them) ÌTÀKÙN TÓ NÍ KÍ ERIN Má
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Agbere wu inaki, aasa wu obo, bi won ti n se nile aye naa wu ara orun #Yoruba #funnysayings
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojúmọ́ ire o. A ò ní kàgbákò lọ́jọ́ òní. A ò ní kọsẹ̀. Àlọ àti àbọ̀ wa wà lọ́wọ́ Ọlọ́run Ọba. Ìfòyà kan kòsí. #ekaaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
pọ́nna pọ́nna ma ń wáyé nínú gbólóhùn nígbà tí gbólóhùn náà bá ní ju ìtumọ̀ kan lọ fún àpẹẹrẹ báyọ̀ na ẹran olójú kan tani olójú kan nínú gbólóhùn yìí ṣé ẹran tí báyọ̀ nà ni tàbí ṣé olówó ẹran náà ni olójú kan pọ́nna ma n gba àlàyé lẹ́kùún rẹ́rẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sọ àwọn ọ̀rọ̀ ní yorùbá pronounce words in yoruba duck pẹ́pẹ́yẹ bird ẹyẹ hen adìẹ pls subscribe to our youtube channel for more link in the bio
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àkókò kò dúró de ẹnìkan time waits for no one make hay while the sun shines promptly exploit opportunities
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Igi rírọ̀ náà lọ jàńtìrẹrẹ. Ara wọn ni a ti rígi Ọ̀mọ̀, Arère, Àfọ̀n àti irúfẹ́ àwọn igi fúyẹ́fúyẹ́ mìíràn bẹ́ẹ̀ tí ó ńbẹ ní ihà ilẹ̀ Yorùbá. Yàtọ̀ sí wí pé igí ní iye lórí púpọ̀, wọ́n jẹ́ ẹ̀dọ̀ fóóró fún ilé ayé #SinkOurCO2 #RiEefinWa @user #Yoruba https://t.co/gFgeju8Tiq
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Araye eyo! Jesu jinde, o segun iku Alleluya! Alleluya! Alleluya!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ajinrĕrĕ Ebenezer Obey, Øba Sunny Ade, KWAM1 abbl ę wa gba ĕĕbu yin ooo. #TweetinYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Níkẹhìn, ìpànìyàn nípasẹ̀ àwọn ọ̀ràn tí ó nira tí ìṣè-ṣe àti iró, 'Hire a Woman' jẹ́ fíìmù tí kò ní idán gidi èyíkèyí.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
a ji ire bi iba akoda iba aseda iba awon to ni aye o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lóòótọ́ àti lododo, kò kúkú sẹ́ni mọ Òkòló nílùú Ọ̀yọ́, kò sẹ́ni mọ apako lásán-làsàn fẹ́ṣin Aláwọ-aàfin. #ItanDowe #Yoruba #Okolo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí akópa ṣe ń fi eegun ta eegun àwọn olùwòran yóò máa kè gídígbò gídígbò wọ́n yó tún fèsì ee yà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ gbọ́ náà ṣé gej àti máa dìbò fún ara wọn ni ọmọdún máàrún kan bi mí |
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
11. Bí ìlà ìbílẹ̀ bá jẹ́ gọ̀mbọ̀, kí ni gọmbọ́? A. Èso B. Ṣíbí kékeré D. Ewéko #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìgbàgbọ́ ìran Yoòbá ni pé oníkálukú wa l'ó ní ẹmẹ̀wà lọ́run kí a tó wá ṣ'áyé. #Asa #EgbeNileYoruba #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní àsìkò àseyorí máse yò láyòju in the time of success dont be overjoyed
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èé ṣe tí òjò fi máa ń rọ̀ lọ́jọ́ kìnínní oṣù èbìbí iṣẹ́ olódùmarè àwámáàrídìí ni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A ò lá ò mọ̀ wípé ẹ̀mí kan ń bẹ tó ju ẹ̀míkẹ́mìí lọ, a mọ̀ pé ní ọ̀run ni ibùdóo Rẹ̀. #YorubaMoOlorun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Akure Oloyemekun! RT @user: Ọmọ #Ondo dà? Ibi ìrìn-àjò ìgbafẹ́ t'ó ń kó èrò wọ #Ondo #WTD @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjọ ọba #SaudiArabia fi ọ̀gbẹ́ni #RaifBadawi si àtìmọ́lé nítorí ó lóun ò ṣ'ẹ̀sìn #Islam mọ́. Mo wá ní, ṣe dandan ni? #FreeRaif
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train