raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
tânia burity tânia cefira gomes burity tí wọ́n bí ní 28 oṣù kẹẹ̀sán ọdún 1978 jẹ́ òṣèrébìnrin olùgbéròyìn atọ́kùn àti afẹwàṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè àngólà ìsẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí burity ní ìlú luanda orílẹ̀-èdè àngólà ó gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ́ ìgbéròyìn láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga instituto médio de economia de luanda imel kí ó tó tún ... |
albertine n'guessan albertine n'guessan zebou lou ó di olóògbé ní 22 oṣù kẹẹ̀rin ọdún 2016 ti jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè côte d'ivoire ìsẹ̀mí rẹ̀ n'guessan kẹ́kọ̀ọ́ ní national institute of arts ina ní ìlú abidjan ní ọdún 1972 ó kópa pẹ̀lú bitty moro aboubakar cyprien touré àti noël guié nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ... |
noufissa benchehida noufissa benchehida tí wọ́n bí ní 23 oṣù kẹẹ̀wá ọdún 1975 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè mòrókò ìsẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí benchehida ní mòrókò ní ọdún 1975 ó fẹ́ràn eré sinimá láti ìgbà èwe rẹ̀ ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé cours florent tí ó wà ní ìlú paris benchehida gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ́ eré-ìtàgé láti ilé-ẹ̀... |
sheila munyiva sheila munyiva tí wọ́n bí ní 27 oṣù kẹẹ̀ta ọdún 1993 jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè kẹ́nyà ìsẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí munyiva ní ọdún 1993 ní ìlú nairobi ó maá n wo eré hannah montana lọ́pọ̀lọpọ̀ nígbà tí ó wà lọ́mọdé ó maá n ṣe àbẹ̀wó sí ilẹ̀ọba aṣọ̀kan lóòrèkóòrè nítorí wípé níbẹ̀ ni ìyá rẹ̀ n ... |
denise newman oṣerebinrin denise newman jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà ìsẹ̀mí rẹ̀ newman dàgbà ní agbègbè athlone tí ó wà ní ìlú cape town òbí rẹ̀ kan jẹ́ olùránṣọ ó ṣe àpèjúwe ara rẹ̀ pé òun maá sábà dá wà nígbà èwe òun tó síì kọ̀ láti rí àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ bá ṣeré lẹ́hìn tí ó parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ láti athlo... |
sana mouziane sana mouziane tí wọ́n bí ní ọdún 1980 jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè mòrókò ìsẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí mouziane ní ìlú casablanca nígbàtí àwọn òbí rẹ̀ kọrawọn sílẹ̀ ó di ẹni tí ó n gbẹ́ ní ìlú marrakesh mouziane lọ sí ìlú lọ́ndọ̀nù nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́sàn-án ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa orin kíkọ ó sì wà ní... |
donia massoud donia massoud tí wọ́n bí ní 2 oṣù kaàrún ọdún 1979 jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè ìjíptì ìsẹ̀mí rẹ̀ massoud lẹni tí wọ́n bí tó sì dàgbà ní ìlú alexandria nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún ó kó lọ sí ìlúkáírò ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akorin àti òṣèré rẹ̀ ní ìlú káírò ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 2000 massoud l... |
souhir ben amara souhir ben amara tí wọ́n bí ní 27 oṣù kọkànlá ọdún 1985 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè tùnísíà ìsẹ̀mí rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú kíkópa nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù bíi maktoub àti choufli hal ní ọdún 2008 ó kópa gẹ́gẹ́ bi maliha nínu eré min ayam mliha ní ọdún 2010 ben amara kó àkọ́kọ́ ipa sinimá àgbélé... |
sandra nkaké sandra nkaké tí wọ́n bí ní ọjọ́ 15 oṣù kọkànlá ọdún 1973 jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù ìsẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí nkaké ní ìlú yaoundé orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù ní ọdún 1973 nígbà tí ó pé ọmọ ọdún 12 ó kó lọ sí orílẹ̀-èdè fráǹsì nkaké ti fẹ́ràn orin kíkọ láti ìgbà èwe rẹ̀ àti pàápàá ó fẹ́ràn okùnr... |
wajiha jendoubi wajiha jendoubi tí wọ́n bí ní ọdún 1972 jẹ́ òṣèrébìnrin àti apanilẹ́rìn-ín ọmọ orílẹ̀-èdè tùnísíà ìsẹ̀mí rẹ̀ jendoubi lẹni tí wọ́n bí ní ọdún 1960 tó sì jẹ́ ọmọ bíbí ìlú kairouan orílẹ̀-èdè tùnísíà ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nípa ìmọ̀ eré ìtàgé ní ọdún 1995 láti ṣe ọ̀kan nínu àwọn ojúṣe rẹ̀ fún ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ jend... |
soumaya akaaboune soumaya akaaboune tí wọ́n bí ní ọjọ́ 16 oṣù kejì ọdún 1974 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè mòrókò ìsẹ̀mí rẹ̀ akaaboune lẹni tí wọ́n bí tó sì dàgbà ní ìlútangier orílẹ̀-èdè mòrókò ìyá rẹ̀ jẹ́ aṣàpẹẹrẹ ẹ̀ṣọ́ aṣọ ní ìgbá tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìnlá òṣe~ré ijó kan tí wọ́n pè ní maurice bejart ṣe àkíyẹ̀sí w... |
mariama sylla mariama sylla faye jẹ oludari fiimu senegalese ati oludasiṣẹ ìsẹ̀mí rẹ̀ wọ́n bí sylla ní ìlú dakar ó síì jẹ́ àbúrò sí ònkọ̀tàn kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ khady sylla ìyá rẹ̀ náà ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ kan tí ó n rí sí sinimá sylla ti ní ìfẹ́ sí eré sinimá ṣíṣe láti ìgbà tí ó wà lọ́mọ ọdún méje nígbà tó jẹ́ wípé wọ́n... |
gertrude webster kamkwatira gertrude webster kamkwatira jẹ́ òṣèré àti olùdarí eré lórílẹ̀-èdè malawi wọ́n bí kamkwatira ní ọdún 1966 ó di adarí fún wakhumbata ensemble theatre ní ọdún 1999 lẹ́hìn ikú olùdásílẹ̀ rẹ̀ lẹ́hìn ìgbà tí ó fi ẹgbẹ́ náà sílẹ̀ ó ẹgbẹ́ wanna-do kalẹ̀ òun ni ààrẹ fún national theater association t... |
aïcha thiam aïcha thiam tí wọ́n bí ní 27 oṣù kẹẹ̀wá ọdún 1979 jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè bẹ́ljíọ̀m àti sẹ́nẹ́gàl |
nidhal guiga nidhal guiga tí wọ́n bí ní 11 oṣù kẹẹ̀ta ọdún 1975 jẹ́ òṣèrébìnrin òkọ̀tàn àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè tùnísíà |
fatou kandé senghor fatou bintou kandé senghor tí wọ́n bí ní 9 oṣù kínní ọdún 1971 jẹ́ olùdarí eré ònkọ̀tàn àti olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè sẹ́nẹ́gàl |
sabrina draoui sabrina draoui tí wọ́n bí ní 24 oṣù kọkànlá ọdún 1977 jẹ́ olùdarí eré àti olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè àlgéríà |
hana el zahed hana el zahed tí wọ́n bí ní 5 oṣù kínní ọdún 1994 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè egypt ìtàn ìgbésí ayé rẹ el zahed a bí ni ọdún 1994 o bẹrẹ èrè ori itage nínú sinima agbelewo al meshakhsaty ni ọdún 2003 ni ọdún 2009o kópa gẹgẹ bí ọmọ ọmọ òṣèré mohamed sobhi nínú ere telifisonu yawmeyat wanees we ahfadoh e... |
laura kutika laura guliamo luyeye kutika tí wọ́n bí ní 24 oṣù kẹẹ̀jọ ọdún 1984 jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè kóngò |
becky ngoma becky ngoma jẹ́ òṣèrébìrin àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè sámbíà ó tún jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde |
henri-joseph koumba bididi henri-joseph koumba bididi èdè lárúbáwá هنري جوزيف كومبا بيديدي tí wọ́n bí ní 15 oṣù keèje ọdún 1957 jẹ́ ònkọ̀tàn àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè gabon tí ó maá n sábà ṣiṣẹ́ lóri àwọn eré ìrírí ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìrírí tó fi mọ́ the king's necklace àti le singe fou |
siatta scott johnson siatta scott johnson tí wọ́n bí ní ọdún 1974 jẹ́ olùdarí àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè làìbéríà ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré aláṣeyọrí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ iron ladies of liberia yàtò sí ṣíṣe olùdarí eré ó tún maá n gbé ìròyìn ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ omuahtee africa media |
marie-clémence paes marie-clémence andriamonta paes tí wọ́n bí ní ọdún 1959 jẹ́ olùdarí eré olùgbéréjáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè fráǹsì àti madagásíkà ó ti ṣe àgbéjáde ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìrírí tó fi mọ́ angano angano mahaleo àti l'opéra du bout du monde |
ladji diakité ladji diakité jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè málì ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí àwọn fíìmù bíi duel à dafa àti fantan fanga yàtò sí dídarí eré diakité tún jẹ́ aṣàpẹẹrẹ aṣọ |
arlete bombe arlete guilhermina guillermina vincente bombe tí wọ́n bí ní ọdún 1983 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè mòsámbìkì |
krischka stoffels krischka stoffels jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàmíbíà krischka ti ṣiṣẹ́ lóri ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó fi mọ́ gesie in die glas àti tjiraaa ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn àti olóòtú fíìmù |
zara mohamed zara mohammed abdulmajid bíi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù keje ọdún 1995 jẹ́ òṣèré mọ́dẹ́lì àti oníṣòwò lórílẹ̀-èdè uganda ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí iman sí ìlú mogadishu ní somalia iman jẹ́ ọmọ mariam àti mohammed abdulmajid bàbá rẹ̀ jẹ́ àmbásẹ́dọ̀ somalia fún orílè-èdè saudi arabia ìyá rẹ sí jẹ́ dókítà ọmọ... |
delphe kifouani delphe kifouani jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè kóngò ó maá n ṣiṣẹ́ olùkọ́ni ní ìmọ̀ sinimá ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga university of saint-louis èyí tí ó wà nísẹ̀nẹ̀gàl |
diana c zollicoffer diana c zollicoffer ọjọ́ìbí 1977 jẹ́ òṣèrébìnrin olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè seychelle ó gbajúmọ̀ jùlọ fún gbígbe àwọn eré bíi schmoolie the deathwatcher bridget and iain àti forgotten bayou jáde |
juliana kanyomozi juliana kanyomozi jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè uganda ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ kanyomozi jẹ́ mọ̀lẹ́bí pẹ̀lú ọba rukidi iv tí ìlú toro bàbá rẹ̀ jẹ́ onílù ìyá bàbà rẹ̀ sí jẹ́ olórin ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ namasagali college iṣẹ́ kanyomozi ní obìnrin olórin àkọ́kọ́ tí ó má gba àmì ẹ̀yẹ tí artist... |
marwa zein marwa zein jẹ́ olùdarí eré ònkọ̀tàn àti olùgbéréjáde lórílẹ̀-èdè sudan òun ni ó kọ ìwé-ìtàn ti ọdún 2019 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ khartoum offside ó maá n lo àwọn iṣẹ́ rẹ̀ láti fi ṣe àgbàwí àti láti fi jà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ agbéré-jáde tí wọ́n pè ní ore production èyí tí ó wà ní ì... |
justine bitagoye justine bitagoye jẹ́ olùdarí eré ònkọ̀tàn àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè bùrúndì ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi agbéròyìn |
mounira mitchala mounira mitchala tí a tún mọ̀ sí sweet panther jẹ́ òṣèrébìnrin akọrin àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè chad |
cleopatra koheirwe cleopatra koheirwe jẹ́ òṣèré olórin àti akọ̀wé lórílẹ̀-èdè uganda ó kópa nínú eré the last king of scotland gẹ́gẹ́bí joy ní ọdún 2006 ó kópa nínú eré sense8 lóri netflix ó ko ipa ebony nínú eré reflections èyí tí nana kagga ṣe adarí rẹ̀ ó darapọ̀ mọ́ startimes uganda ní oṣù kẹfà ọdún 2019 bí ìkan lár... |
mosili makuta mosili makuta jẹ́ òṣèrébìnrin lórílẹ̀-èdè lèsóthò |
flora gomes flora gomes jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè guinea-bissau wọ́n bi ní ìlú cadique orílẹ̀-èdè guinea-bissau ní ọjọ́ 31 oṣù kejìlá ọdún 1949 ó lọ ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè kúbà ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ fíìmù ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga instituto cubano del arte y la industria cinematográficos èyí tí ó wà ní ìlú ... |
yéyamba wandzé mdrou ndo yéyamba wandzé mdrou ndo jẹ́ eré aláwàdà kan ti orílẹ̀-èdè comoros tí wọ́n ṣe ní ọdún 2000 èyí tí adarí rẹ̀ n ṣe arsin soiby fíìmù náà ni àkọ́kọ́ fíìmù gígùn ti comoros |
nous aurons toute la mort pour dormir nous aurons toute la mort tú dormir jẹ́ eré ti ọdún 1977 lórílẹ̀-èdè mauritáníà èyí tí med hondo ṣé adarí rẹ̀ wọ́n bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe fíìmù náà láti 25 oṣù kejìlá ọdún 1975 títí di 5 oṣù kẹẹ̀ta ọdún 1976 fíìmù náà dá lóri akitiyan àwọn ẹgbẹ́ polisario front láti bọ́ nínu oko-ẹrú ọwọ́ oríl... |
teresa 2010 film teresa jẹ́ fíìmù oníṣókí kan ti ọdún 2010 tí wọ́n ṣe ní equatoial guinea tí olùdarí rẹ̀ n ṣe thato rantao mwosa èyí tí ààjo ilé-ìkàwé orílẹ̀-èdè equatorial guinea ṣe onígbọ̀wọ́ rẹ̀ guillermina mekuy mba obono lẹni tí ó kọ ìtàn eré náà àwọn olùkópa rẹ̀ pẹ̀lú elena iyanga betty kb àti dina anguesomo eré ... |
lula ali ismaïl lula ali ismail tí wọ́n bí ní ọdún 1978 jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè djibouti àti canada òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti gbé eré jáde lórílẹ̀-èdè djibouti ó ṣe adarí eré oníṣókí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ laan ní ọdún 2011 wọ́n wo fíìmù náà níbi ayẹyẹ vues d'afrique festival tí ó wáyé ní ìlú montreal ... |
umshana umshana ni eré ti ọdún 2015 kan tí wọ́n ṣe lórílẹ̀-èdè eswatini tí olùdarí rẹ̀ n ṣe bi phakathi èyí tí ilé-iṣé bip films ṣètò àgbéjáde rẹ̀ àwọn olùkópa eré náà pẹ̀lú mbali dlamini delani dlamini lisa mavuso temakhosi nkambule àti fineboy mhlanga èyí ni àkọ́kọ́ fíìmù tí wọ́n máa ṣe lédè swati gbogbo ṣíṣe eré náà... |
vivienne roumani vivienne roumani-denn tí wọ́n bí ní ọdún 1950 jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè líbyà ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré the last jews of libya àti out of print |
fathia absie fathia absie jẹ́ òṣèrébìnrin ònkọ̀tàn olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè sòmálíà àti amẹ́ríkà ó ti ṣiṣẹ́ lóri ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìrírí àti àwọn eré àròṣe ó sì ti kọ ìwé-ìtàn kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ the imperceptible peace maker |
rehema nanfuka rehema nanfuka bíi ni ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1986 jẹ́ òṣèré àti adarí lórílẹ̀-èdè uganda tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínú eré imani veronica's wish imbabazi haunted souls the road we travel papi tropical fish slay queen of africa queen of katwe àti imperial blue iṣẹ́ ipa tí ó kó nínú eré m... |
malaika tenshi malaika tenshi nnyanzi tí orúkọ ìnagi rẹ̀ jẹ́ malaika jẹ́ òṣèré mọ́dẹ́lì àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ èdè uganda ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí atọ́kun fún ètò d'mighty breakfast lórí kfm àti ètò malaika àti oulanya lórí capital fm ó ti kópa nínú eré and iṣẹ́ malaika bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ mọ́dẹ́lì ní ìlú nairobi lórílẹ̀ èdè ... |
anne kansiime kansiime kubiryaba anne bíi ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 1986 tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí anne kansiime jẹ́ òṣèré àti aláwàdà lórílẹ̀ èdè uganda ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí anne sí ìlú mparo ní àgbègbè kabale district ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ kabale primary school àti bweranyangi girls' secondary schoo... |
akite agnes akite agnes bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹta ọdún 1983 jẹ́ òṣèré àti aláwàdà lórílẹ̀-èdè uganda ẹ̀kọ́ rẹ̀ akite gboyè nínú tourism láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí makere university iṣẹ́ ní ọdún 2014 akite bẹ̀rẹ̀ àwàdà ṣíṣe pẹ̀lú ẹgbẹ́ the punchliners ní ọdún 2016 ó kópa nínú eré girl from mparo gẹ́gẹ́ bí mama bria... |
anita fabiola anita kyarimpa jẹ́ òṣèré atọkun ètò àti oníṣòwò lórílẹ̀ èdè uganda ní oṣù kejì ọdún 2019 ilé iṣẹ́ goodwill tourism fi ṣe àmbásẹ́dọ̀ wọn kí ó tó ṣe atọ́kun fún ètò bẹ my date lórí ntv ní ọdún 2014 ó ti jẹ ipò omidan uganda tí apá iwọ̀ òrùn ó gbé ipò kejì níbi ìdíje omidan uganda ó ti ṣe atọ́kun fún àwọn ay... |
barlen pyamootoo barlen pyamootoo tí wọ́n bí ní 27 oṣù kẹẹ̀sán ọdún 1960 jẹ́ olùgbéré-jáde olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè mauritius ó gbajúmọ́ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ bénarès |
étienne goyémidé étienne goyémidé 22 oṣù kínní ọdún 194217 oṣù kẹẹ̀ta ọdún 1997 jẹ́ ònkọ̀wé àti ònkọ̀tàn eré ọmọ orílẹ̀-èdè olómìnira àrin áfríkà ó gbajúmọ̀ fún kíkọ àwọn ìwé-ìtàn tí àkọ́lé wọ́n jẹ́ le silence de la forêt àti dernier survivant de la caravane |
nyakuron cultural centre nyakuron cultural centre ncc ni ilé-iṣẹ́ kan tó n ṣe ti ìjọba tí wọ́n dá sílẹ̀ láti máa ṣètò mímú ìdàgbàsókè àti ìgbéga bá sinimá àti àṣà orílẹ̀-èdègúúsù sudan |
mionga ki ôbo mionga ki ôbo tàbí mionga ki ôbo mar e selva ni fíìmù ti ọdún 2002 kan tí wọ́n ṣe lórílẹ̀-èdè são tomé and príncipe tí olùdarí rẹ̀ n ṣe ângelo torres tí luis correia àti noé mendelle síì dì jọ ṣe àgbéjáde rẹ̀ láti ilé-iṣẹ́ lx filmes fíìmù náà dá lóri ìrìn-àjò àwọn olùgbé àtijọ́ ti erékùsù são tomé tí wọ́n... |
figueira cid figueira cid tí wọ́n bí ní 18 oṣù kínní ọdún 1957 jẹ́ òṣèrékùnrin olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè pọ́rtúgàló ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ilẹ̀ yúróòpù àti ilẹ̀ áfríkà ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ nínu àwọn fíìmù bíi ministério do tempo até amanhã camaradas àti the masked avenger lagardère |
stefanos pavlakis stefanos pavlakis tí wọ́n bí ní ọdún 1974 jẹ́ olùdarí eré ònkọ̀tàn àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè gíríìsì ó ti lọ́wọ́sí tó sì ti nípa lọ́pọ̀lọpọ̀ nínu àwọn sinimá orílẹ̀-èdè bẹ̀nìn pẹ̀lú ṣíṣe àwọn fíìmù ìtàn-àkọọ́lẹ̀ bíi the eye of the beholder studio harmattan àti drive through |
marc serena marc serena tí wọ́n bí ní ọdún 1983 jẹ́ olùgbéré-jáde olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè spain ó gbajúmọ̀ fún dídarí àwọn fíìmù ìtàn-àkọọ́lẹ̀ ti ilẹ̀ áfríkà bíi tchindas peixos d'aigua dolça àti the writer from a country without bookstores |
pablo césar pablo césar tí wọ́n bí ní 26 oṣù kínní ọdún 1962 jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè argẹntínà ó ti lọ́wọ́sí sinimá ilẹ̀ áfríkà pẹ̀lú dídarí àwọn eré bíi equinox the garden of the roses los dioses de agua àti aphrodite the garden of the perfumes |
cecilia zoppelletto cecilia zoppelletto jẹ́ olùdarí eré lóbìnrin àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè itálíà ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré ìtàn-àkọọ́lẹ̀ kan lórílẹ̀-èdè kóngò èyí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ la belle at the movies |
ernest napoleon ernest napoleon jẹ́ òṣèrékùnrin àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè rọ́síà àti tànsáníà |
rẹ̀mí àlùkò adérẹ̀mí àlùkò tí gbogno ènìyàn tún mọ̀ sí igwe bàbá àràbà àjélà' àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ jẹ́ olórin ọ̀kọrin fújì àti òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgba èwe rẹ̀ wọ́n bí rẹ̀mí àlùkò ní ìlú èbúté mẹ́ta ní ìpínlẹ̀ èkó ní ọdún 1977 àmọ́ àwọn bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú iléṣà ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun tí ìyá rẹ̀ sì jẹ... |
ariane astrid atodji ariane astrid atodji tí wọ́n bí ní ọdún 1980 jẹ́ olùdarí eré olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdèkamẹrúùnù ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ tó fi mọ́ koundi et le jeudi national àti la souffrance est une école de sagesse |
claude haffner claude haffner tí wọ́n bí ní ọdún 1976 jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè fráǹsì àti kóngò ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ tó fi mọ́ ko bongisa mutu défilé célianthe àti noire ici blanche là-bas |
muka ray mukadas ray eyiwumi tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí muka ray ni ó jẹ́ ọmọ bíbí gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé ray èyíwùnmí tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹrin ní òpópónà olúsọjí ní ìlú bàrígà ní ìpínlẹ̀ èkó àmọ́ tí ó àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìrẹ́pọ̀ọ́dùn ní ìpínlẹ̀ kwara jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé a... |
manouchka kelly labouba manouchka kelly labouba jẹ́ olùdarí eré olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ́ orílẹ̀-èdè gàbọ̀n tó maá n sábà daŕi àwọn eré oníṣókí ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníṣókí lára wọn ni marty et la tendre dame le guichet automatique àti le divorce ó tún maá ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olóòtú sinimá àti olùyàwòrán |
kalifa dienta kalifa dienta tí wọ́n bí ní 1 oṣù kínní ọdún 1940 jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè málì ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ a banna ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn àti olùyàwòrán |
hind bensari hind bensari tí wọ́n bí ní ọdún 1987 jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè mòrókò ó gbajúmọ̀ fún dídarí àwọn eré bíi 475 break the silence àti we could be heroes |
aïcha macky aïcha elhadj macky 8 oṣù kínní ọdún 1982 jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nìjẹ̀r ó tún jẹ́ onímọ̀ nípa àwùjọ ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ the fruitless tree |
musanase laura musanase laura tí wọ́n bí ní ọdún 1993 jẹ́ òṣèrébìnrin lórílẹ̀-èdè rùwándà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè rùwándà látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré tẹlifíṣọ̀nù aláwàdà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ city maid |
munezero aline munezero aline tí wọ́n bí ní ọdún 1994 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè rùwándà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi milika nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ gica |
mukakamanzi beatha mukakamanzi beatha jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdèrùwándà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ giramata gẹ́gẹ́ bi ìyá sí giramata |
nadege uwamwezi nadege uwamwezi tí wọ́n bí ní ọdún 1993 jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè rùwándà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tẹlifíṣọ̀nù tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè rùwándà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi nana nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ city maid ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi aṣàpẹẹrẹ ẹ... |
bahavu jeannette bahavu usanase jeannette jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn ọmọ orílẹ̀-èdè rùwándà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi diane nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ city maid ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi aṣàpẹẹrẹ ẹ̀ṣọ́ aṣọ |
kirenga saphine saphine kirenga jẹ́ obìnrin osere ara rùwándà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tẹlifíṣọ̀nù tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè rùwándà ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù bíi the chains of love dreams sakabaka rwasibo seburikoko urugamba àti the secret of happiness ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ ìlera |
pascale lamche pascale lamche tí wọ́n bí ní oṣù keèje ọdún 1960 jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdèfránsì àti gúúsù áfríkà ó gbajúmọ̀ fún dídarí àwọn eré tí ó lórúkọ bíi stalingrad black diamond pakistan zindabad french beauty accused #1 nelson mandela sophiatown àti winnie ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ònkọ... |
lásún ray 'ọlásúnkànmí ray èyíwùmí tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí lásún ray jẹ́ ọmọ bíbí ògbóntagì òṣèré yorùbá tí ó ti di olóògbé pa ray èyíwùmí ó jẹ́ òṣèré adarí eré ati olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgba èwe àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí súnkànmí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kíní ní ìpínlẹ̀ kwara ó kẹ́kòọ́ gboyè jáde n... |
waris dirie waris dirie bíi ni ọdún 1965 jẹ́ mọ́dẹ́lì òṣèré àti ajìjàgbara lórílẹ̀-èdè uganda ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí dirie ní ọdún 1965 ó ṣì jẹ́ ìkan lára àwọn ọmọ méjìlá tí àwọn òbí rẹ bí nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́tàlá ó sá kúrò nílé nítorí àwọn ẹbí rẹ̀ ní kí ó fẹ́ arákùnrin kan tí ó jẹ́ ọmọ ọgọ́ta ọdún wọ́... |
xolile tshabalala xolile tshabalala tí wọ́n bí ní 9 oṣù kẹẹ̀rin ọdún 1977 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù bíi 4play sex tips for girls secrets scandals blood water àti housekeepers ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí xolile ní ọdún 1977 ní ìlú vrede èyí tí ó wà ní ìgb... |
malaika uwamahoro malaika uwamahoro bíi ni ọdún 1990 jẹ́ òṣèré akéwì olórin àti ajìjàgbara lórílẹ̀ èdè rwanda ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí malaika sí rwanda ní ọdún 1990 nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó wáyé ní ọdún 1994 òun àti ìyá rẹ sá kúrò ní rwanda lọ sí uganda ó gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí fordham un... |
thembi mtshali-jones thembi mtshali-jones tí wọ́n bí ní 7 oṣù kọkànlá ọdún 1949 jẹ́ òṣèrébìnrin akọrin àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù bíi sgudi 'snaysi stokvel silent witness àti imbewu ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olùkọ́ ní global arts corps èyí tí ó wà ní... |
blandine yaméogo blandine yaméogo tí wọ́n bí ní ọdún 1960 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè bùrkínà fasò ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó lórúkọ tó fi mọ́ la nuit de la vérité delwende àti notre étrangère ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi oníjó |
letekidan micael letekidan micael tí wọ́n bí ní ọdún 1997 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè ẹritrẹ́à ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi 'awet' nínu fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ feuerherz ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bi ní ọdún 1997 ní ìlú asmara orílẹ̀-èdè ẹritrẹ́à lẹ́hìn tí ó kópa nínu eré ológun tí a pe àkọ́lé rẹ̀ ní feuerhe... |
tariro mnangagwa tariro washe mnangagwa tí wọ́n bí ní ọdún 1986 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè sìmbábúè ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré kan ti ọdún 2020 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ gonarezhou ó jẹ́ ọ̀kan nínu àwọn ọmọ obìnrin ààrẹ orílẹ̀-èdè sìmbábúè lọ́wọ́lọ́wọ́ ti orúkọ rẹ̀ n ṣe emmerson mnangagwa ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ wọ... |
dorra zarrouk dorra ibrahim zarrouk lárúbáwá bíi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní ọdún 1980 jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè tunisia ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí dorra sí ìlú tunis bàbá rẹ̀ ni ibrahim zarrouk bàbà ìyá rẹ̀ sì ni ali zouaoui tí ó jẹ́ òṣèlú dorra gboyè nínú ìmò òfin àti òṣèlú láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí saint joseph universi... |
danieline moore danieline moore kamya jẹ́ òṣèré àti oníṣòwò lórílẹ̀ èdè liberia ní ọdún 2007 ó di omidan liberia iṣẹ́ ní ọdún 2006 ó lọ fún ìdíje omidan liberia tí amẹ́ríkà ṣùgbọ́n ó gbé ipò kẹrin níbẹ̀ ní ọdún tó tẹ̀le ó tún kópa nínú ìdíje náà ó ṣì gbé ipò kìíní ó kopa nínú eré crazy in love pẹ̀lú àwọn òṣèré bíi jim ... |
rym breidy rym saidi breidy lárúbáwá bíi ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà ọdún 1986 jẹ́ mọ́dẹ́lì àti òṣèré lórílẹ̀-èdè tunisia iṣẹ́ rym breidy bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí mọ́dẹ́lì ní ọdún 2003 lẹ́hìn tí ó gbé igbá orókè níbi ìdíje elite model look tunisia ní ọdún 2006 ó gbé ipò kìíní níbi ìdíje mission fashion ní ọdún 2007 ó d... |
flora suya flora suya jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè malawi wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ kẹfà àti kẹsàn-án tí african movie academy awards iṣẹ́ suya kópa nínú eré seasons of a life ní ọdún 2010 pẹ̀lú tapiwa gwaza gẹ́gẹ́ bí ọmọ ọ̀dọ̀ tí ọ̀gá rẹ̀ má ń fi ipá ba lòpọ̀ ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù... |
jesesi mungoshi jesesi mungoshi jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè zimbabwe iṣẹ́ mungoshi kópa nínú eré african journey ní ọdún 1989 pẹ̀lú àwọn òṣèré bíi jason blicker katja blomquist allan jordan àti ulla mahaka ní ọdún 1991 ó kó ipa neria nínú eré neria èyí tí godwin mawuru gbé kalẹ̀ òun àti àwọn òṣèré bíi yemi goodman ajibade be... |
henrietta mbawah henrietta mbawah jẹ́ òṣèré àti ajìjàgbara lórílẹ̀-èdè sierra leone ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí olùdarí eré eré jattu àti fún ipa tí ó kó nínú eré ebola checkpoint iṣẹ́ ní ọdún 2016 mbawah gbé eré rán pé jattu kalẹ̀ eré náà sọ̀rọ̀ nípa ọmọbìnrin jattu tó ṣẹ́gun àrùn ebola ní áfríkà ní ọdún náà ó kó ipa oníróyì... |
zainab jah zainab jah jẹ́ òṣèré orí ìtàgé tẹlẹfíṣọ̀nù àti fíìmù lórílẹ̀-èdè sierra leone ó gbajúmọ̀ fún ipa maima tí ó kó nínú eré eclipsed ó kó ipa aminata sissoko nínú eré deep state àti aby bah nínú eré homeland wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òséré tó tayọ jùlọ ní ọdún 2019 láti ọ̀dọ̀ drama desk award |
wally adéyẹmọ adéwálé wally adéyẹmọ wọ́n bí i lọ́dún 1981 jẹ́ ààrẹ àkọ́kọ́ fún àjọ-aṣàánú obama foundation tí ààrẹ àná orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà barack obama dá sílẹ̀ during the obama administration adéyẹmọ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí igbákejì olúdámọ̀ràn lórí ètò àbò fún àjọ ètò ọ̀rọ̀-ajé àgbáyéinternational economics lórílẹ̀-èdè amẹ́r... |
austin abrahams american actor austin noah abrams tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹsàán ọdún 1996 jẹ́ òṣèré ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré onípele àtìgbà-dégbà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtan ron anderson nínú ìpele ẹlẹ́kaàárùn ún eré the walking dead 20152016 tí ó sì tún kópa nínú eré euphoria gẹ́gẹ́ ... |
asher angel asher dov angel tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹsànán ọdún 2002 jẹ́ òṣèrékùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2008 níbi tí ó ti kópa nínú eré jolene eré tí jessica chastain náà ti kópa ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí jonah beck nínú eré onípele disney channel ní ọdún 2017 ... |
iris apatow american actress iris apatow tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹwàá ọdún 2002 jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn arya nínú eré onípele tí wọ́n ń ṣàfihàn rẹ̀lórí ìkanì netflix tí akòrí rẹ̀ ń jẹ́ love òun náà ló tún kópa ẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn charlotte nínú eré kno... |
ariela barer ariela barer tí wọ́n bí ní ọjọ́ oṣù kẹrìnlá oṣù kẹwàá ọdún 1998 jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà tí ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré hulu tí ó jẹ́ ìpele runaways gẹ́gẹ́ bí gert yorkes ìgbà èwe rẹ̀ àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ jew theirẹ̀gbọ́n rẹ̀ libe barer náà jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé iṣẹ́ rẹ̀ ariela... |
sofia black d-e'lia sofia black-d'elia tí wọ́n bí ní inú oṣù kejìlá ọdún 1991 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn tea marvelli nínú eré skins sage spence nínú eré gossip girl ati andrea cornish nínú eré the night of láàrín ọdún 2017 sí 2018 black-d'elia kóp... |
asher blinkoff american child actor and voice actor asher blinkoff tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kọkànlá ọdún 2008 òṣèrémọdé ọkùnrin tí ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré hotel transylvania film franchise gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn dennis fún ilé-iṣẹ́ columbia picturesàti sony pictures animation iṣẹ́ rẹ̀ asher ... |
wema sepetu wema sepetu bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1990 jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè tanzania iṣẹ́ ní ọdún 2011 ó gbé eré superstar kalẹ̀ tí ó sọ̀rọ̀ nípa ìtàn ìfẹ́ òhun àti diamond platnumz ní ọdún 2014 òun àti van vicker jọ gbé eré day after death jáde ní ọdún 2013 ó gbé ilé iṣẹ́ rẹ̀ kalẹ̀ tí ó pè ní endle... |
beatrice taisamo beatrice taisamo jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè tanzania ó kó ipa tula nínú eré siri ya mtungi ó kó ipa fatuma nínú eré hadithi za kumekucha fatuma èyí tí jordan river gbé kalẹ̀ ní ọdún 2018 wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ amaa ní ọdún 2019 fún ipa tí ó kó nínú eré náà |
kajala masanja kajala masanja bíi ni ọjọ́ kẹjìlélógún oṣù keje jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè tanzania ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ east television award ní ọdún 2016 ó kópa nínú eré kijiji cha tambua haki pẹ̀lú steven kanumba o jẹ iyawo fun faraji chambo |
chaste christopher inegbedion chaste christopher inegbedion tí wọ́n bí ní agbègbè ìlú muṣin ní ìpínlẹ̀ èkó jẹ́ gbajú-gbajà olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ara ẹni ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe ti creative5 ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ christopher lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ yunifásitì ọlábísí ọnàbánjọ oou tí ó wà ní ìpínlẹ̀ ògùn lẹ́y... |
lena belkina lena belkina ojoibi 27 november 1987 tashkent ìsọ̀kan sófìẹ̀tì je olorin omo ile ukraníà |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.