raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
brítánì |
àtòjọ àwọn ìwé àpilẹ̀kọ ajẹmábo àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn ìwé àpilẹ̀kọ ajẹmábo a tò wọ́n nípa ọdún tí wọ́n kọ wọ́n àti bí àwọn àkọlé wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn ní ìlànà ábídí |
lara and the beat 2018 nigerian film lara and the beat jẹ́ eré-onítàn orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jáde ní ọdún 2018 tí tosin coker jẹ́ olùdarí fíìmù náà àwọn akópa fíìmù náà ni seyi shay vector somkele iyamah wale ojo sharon ooja shafy bello-akinrimisi àti uche jombo ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án ọdún 2018 ni wọ́n ṣàgbéjade fíìm... |
timo werner timo werner tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1996 6th march 1996 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-èdè germany tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù-jẹun lórílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì fún ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá chelsea werner bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá jẹun gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n fún ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù... |
omo elesho omo elemosho english child of elemosho jẹ́ èré órì tágè tì ìlù ńáìjírìá ńì ọ̀dùń 2012 tì báyò tìjáńì jẹ́ òlùdárì rẹ́ átì yèwáńdè ádèkòyá jẹ́ èńì tì ò gbè èré ńà jádè tì ò sì tùńjè èńì tì ò gbá àmì ẹ́yẹ̀ fùń èré káń tì ò gbè jádé tì òrùkọ̀ ńáà sìńjẹ́ kùdì klẹ́ptò ọ́mọ̀ ẹ́lẹ́shọ̀ gba ami ẹ́yé márùń ńìńù idi je... |
al abdul majeed abdul latiff abdul majeed 15 oṣù kọkànlá odun1933 13 kọkànlá oṣù 1987 jẹ oloselu sri lankan ati ọmọ igbimọ aṣoju ibẹrẹ igbesi aye re won bi abdul majeed ni ojo karun-dinlogun oṣù kọkànlá odun 1933 o kọ ẹkọ ni sivananda vidyalayam batticaloa ati trincomalee hindu college lẹhinna o kọ ẹkọ ni ile-ẹkọ giga ... |
abeni 2006 nigerian romance filmabeni je ere oni se ti won gbe jade ni orilede najaria ati benin ni odun 2006 tunde kelani si je olu gbere-jade ati aderi ere naa |
àtòjọ àwọn ilé ìjọsìn ṣọ́ọ̀ṣì ní nàìjíríà orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni orílẹ̀ èdè kejì tí ó ń sin ọlọ́run jùlo ní àgbáyé gẹ́gẹ́ bí ìwádìí ti pew research ṣe sọ ẹ̀sìn méjì àwọn ọmọ nàìjíríà ń ṣe jù lọ àwọn tí apá àríwá ń ṣe ẹ̀sìn mùsùlùmí tí àwọn ti iwọ̀ oòrùn ń ṣe ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn ṣọ́ọ̀ṣì tó gbajúmọ̀ ... |
king of boys king of boys jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jáde ní ọdún 2018 tí ó dálé lórí ọ̀ràn dídá àti ìjàkadì fún agbára àti ipò kemi adetiba ló kọ fíìmù yìí òun sì ni ó darí rẹ̀ tí ó sì gbe jáde pẹ̀lú fíìmù yìí jẹ́ fíìmù ẹlẹ́ẹ̀kejì tí arábìnrin kemi adetiba gbé jáde lẹ́yìn tí ó gbé the wedding party jáde fíìmù ... |
beverly adams they had four children daughter catya 19682002 an actress who died from a drug-induced heart attack son elan benvidal b january 17 1970 son david b ca 1972 and daughter eden sassoon born ca 1973 beverly adams sassoon ti a bi ni oṣu kẹwa ọjọ 7 ọdun 1945 jẹ oṣere ati onkowe ara ilu amẹrika ati canada ibere ... |
komadugu gana river the komadugu beôeô river tábì odó misau jẹ́ odò́ nì ílù chad basin nì árìwà nigeria tì parapó mọ yobe river nì damasak nì mobbar agbègbè ìjọba borno state ó selẹ̀ ní àríwá bauchi gẹ́gẹ́bí ìjábọ̀ 2011 ńipasẹ̀ international union fún conservation of nature ṣíṣàn omi odò ýi kò dé yóbè mọ́ a ṣe àwárí ọk... |
ojú kòkòrò 2016 nigerian film ojú kòkòrò greed jẹ́ eré sinimá agbéléwò tí ó jẹ́ àkójọ àwọn eré crime-heist comedy film tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2016 tí àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bíi wale ojo tope tedela charles etubiebi seun ajayi shawn faqua ali nuhu somkele iyamah emmanuel ikubese àti afeez oyetoro ti kópa dáre ọláìtán ni ... |
the cleanser ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ cleanser2021 nigerian thriller film by mathew alajoguncleanser jẹ fiimu igbadun ti won gbe jade ni orilẹ-ede naijiria ni odun 2021 ti mathew alajogun se ako sile re james abinibi si gbe ere naa jade awon olukopa tabi eda-itan inu ere naa ni kehinde bankole bolanle ninalowo alex osif... |
wale ojo nigerian actor ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ wole ojo wale ojo jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti britain ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣẹ láti ìgbà tó wà lọ́mọdé lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ó tẹ̀síwájú láti máa ṣe eré ní uk àti nàìjíríà ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 1995 fún kíkópa tí ó kópa nínú fíìmù the hard case ó gba àmì ẹ̀yẹ fún òṣèr... |
mother of george mother of george jẹ́ ere ońìṣè kan ni ọ̀dùń 2013 ńì órìlẹ́-èdé ńáìjírì tì andree dòsùńmù jẹ́ òlùdárì rẹ́ directed byandrew dosunmuèré yì sọ̀ ńìpá igbeyawo tuntun káń tì wọ̀ń wá látì orìlè-èdé ńáìjìríá tì wọ̀ń sìńgbè ńì òkè ókùń ńì órìlè-èdé broklìń tì wọ̀ń ńì ìlè íṣẹ́ káń tì áwọ̀ń èyáń jẹ́ tì wọ̀ń sì m... |
àtòjọ àwọn òjíṣẹ́ ọlọ́run pásítọ̀ ní nàìjíríà |
saidat adegoke sàìdát adégòkè tí a bí ní ọjọ́ kerìnlélógún oṣù kẹsàn-án oṣù òwewè ọdún un 1985 ní ìlú ìlorin ìpínlẹ̀ kwara nigeria jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ re ní ọdún 2007 adégòkè bẹ̀rẹ̀ sí ní ń gbá bọ́ọ̀lù fún rẹ́mọ queens láti ìlu rẹ̀ nàìjíríà ní ipele serie a ti orílẹ̀-èdè italy fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ... |
ayitale 2013 nigerian drama filmayitale je ere oni se ti won gbe jade ni orilrde naijiria ni odun 2013 adebayo salami je olu gbere jade ati oludari ere ere naa gba ami eye ere to daraju ni nollywood ni odun odun 2013 |
the hard case the hard case jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè britain tí ó jáde ní ọdún 1995 guy ritchie ni ó kọ fíìmù yìí tí ó sì tún darí rẹ̀ àwọn akópa fíìmù yìí ni darren spencer tí ó ṣe the player benedick bates tí ó ṣe player àti wale ọjọ́ tí ó ṣe gambler fíìmù ogún ìṣẹ́jú yìí gbéwọ̀n ju fíìmù ritchie kan tí í ṣe lock stock a... |
oga bolagi 2018 nigerian drama filmoga bolaji jẹ́ èré óńìṣè kan lati orile-ede ńáìjírìá ńì ọ̀dùń 2018 tì ọ̀táń átì ólùdárì jẹ́ kanọ̀dè ka su mu èré yì ṣè áfìháń ikponmwosa gold omowumi dada átì idowu philips gẹ́gẹ̀ bi olù ẹ́dá ítáń èré óńíṣè yí jádé ńí ọ̀jọ̀ kèjé oṣù kejè ọ̀dùń 2018 tì áwọ̀ń irísì àwọ̀ń èyáń ńìpá èré ń... |
code of silence code of silence jẹ́ eré oníṣẹ́ tí bola aduwo kọ tí òṣèré olùgbéré-jáde emem isong gbé jáde ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní 2015 royal art art academy ati nollywood workshop fọwọ́sowọ́pọ̀ gbé jáde wọ́n bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú makida moka ẹni tí ó jẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn tí ó kópa gẹ́gẹ́ bí adanma eré yí da lé ìtako ìwà ìfipá b... |
amenze aighewi amenze aighewi tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1991 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà kan tí o ń gbá ọwọ́ iwájú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè naijiria ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ti o gbá bọ́ọ̀lù nínú ìdíje fifa world cup ti ọdún 2011 o gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ rivers angel ní ìpínlẹ̀ rivers ní o... |
nigerian people's party ẹgbẹ́ òṣèlú nigerian peoples party npp jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn ẹgbẹ́ẹ́ òṣèlú tí wọ́n ìdíje sípò ase nígbà ìṣèjọba alágbádá ẹ́lẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ẹgbẹ́ òṣèlú yí ni ó jẹ́ àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ àwọn ni lagos progressive club 19 àti nigerian council of understanding tí ... |
mokalik 2019 nigerian comedy drama film by kúnlé afọláyan mokalik jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ elédè méjì tí a gbé jáde ní ọdún 2019 kúnlé afọláyan ni olùdarí àti ẹni tí ó gbé fíìmù yìí jáde fíìmù náà ṣe àfihàn toni afolayan tí ó ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe tí ó jẹ́ olú ẹ̀dá ìtàn lọ́kùnrin pẹ̀lú fẹ́... |
abobaku abobaku jẹ fiimu kukuru ti won se ni 2010 nipasẹ femi odugbemi ati oludari ni niji akannii fiimu naa gba ami eye fiimu to ta yo ni nu awon fiimu to kukuuru ju ni igba gede zuma film festival ni odun 2010 ati ami eye fun eso ti o dara julọ ni ibi ayeye ’’africa movie academy awards’’ ele kefa iru e ti o waye ni ... |
the virgin the virgin jẹ́ íwé tì o tájù ńì ọ̀dùń 1985 tì báyọ̀ adebowale je ákọ̀wè nábayo adebowale íwé tì wọ̀ń ṣè átẹ̀jádè rẹ̀ ńì ọ̀dùń 1985sọ̀ ńìpá wàálá tì óbìńrìń káń dójùkọ̀ ńì ìlú rẹ̀ ńìpá kì ómù íkáń lárà áwọ̀ń ókùńrìń mẹ́tá káń tìwọ̀ń dà èńù ífẹ̀ sì tí wọ̀ń mọ̀ pè ótìjábàlé tábì kí áwọ̀ń tù áṣírì ẹ́ ńí álè ìgbè... |
àtòjọ àwọn oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ wikipedia list article awon wọ̀nyí ni àtòjọ tòjọ àwọn oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ áfíríkà ilẹ̀ áfíríkà jẹ́ ilẹ̀ kejì tó tóbi jù ní àgbáyé pẹ̀lú oríṣiríṣi àṣà ẹyà àti ènìyàn pẹ̀lú oríṣiríṣi oúnjẹ àwọn ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ló sìn ní oúnjẹ kọ̀ọ̀kan wọn àwọn nǹkan tí wọ́n fi ń sè é and bí wọ́n ṣe ń sè é |
mainframe films and television productions mainframe films and television productions eyiti a mọ ni mainframe studios tabi mainframe films jẹ ile-iṣẹ iṣelọpọ fiimu ti won da si le ni 1991 nipasẹ oṣere fiimu fiimu ti nigeria ati olupilẹṣẹ fiimu tunde kelani lati igba idasilẹ ni ọdun 1991 ile-iṣẹ iṣelọpọ ti ṣe ọpọlọpọ aw... |
àtòjọ àwọn ẹ̀yà nàìjíríà list article of ethnic groups in the african country of nigeria orílẹ̀ èdè nàìjíríà jẹ́ ilẹ̀ tí ó kún fún oríṣiríṣi ẹ̀yà tí ó ju 250 pẹ̀lú èdè tí ó tó bí i 500 list of ethnic groups the following is a non-exhaustive list of ethnic groups in nigeria |
family on fire family on fire jẹ́ eré tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2011 tí tade ogidan darí rẹ̀ àwọn gbajú-gbajà òṣèré bíi saheed balogun segun arinze sola fosudo àti sola sobowale ni wọ́n kópa nínú rẹ̀ wọ́n ṣàfihàn fiimu náà ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 2011ní gbọ̀ngàn lighthouse ní camberwell ní ìlú london lara àwọn gb... |
irapada irapada english redemption jẹ́ eré adẹ́rùbani tí wọ́n gbé jáde ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2006 tí kunle afolayan sì jẹ́ olùdarí eré náà ní ọdún 2017 eré náà gba amì-ẹ̀yẹ africa movie academy award for best film in an african language fiimu náà tún wà lara àwọn eré tí wọ́n gba amì-ẹ̀yẹ best african films of ... |
marsha hunt marcia virginia hunt ojoibi oṣù kẹ̀wá 17 1917 je osere ara amerika |
cher lloyd cher lloyd jẹ akọrin ilu gẹẹsi kan yi ni a kukuru article jọwọ mu yi |
jagua nana jagua nana ni ìwé àkàgbádùn tí cyprian ekwensi kọ ní ọdún 1961 wọ́n kọ́kọ́ gbé ìwé yí jáde ní ọdún 1975 lábẹ́ ilé-iṣẹ́ heinemann african publisher ìwé yí da lórí iyè-méjì tí ó ń ṣẹlẹ̀ẹ̀ nínú ayé obirin tí ó jẹ́ olówò nàbì tí ó ti ń dàgbà jagua nana tí ó jẹ́ olú-èdá ìtàn the novel is set in the city of lagos ... |
419 novel 419 ni ìwé àkàgbádùn tí ọmọ orílẹ̀-èdè canada tí ó ń jẹ́ will ferguson kọ tí ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé penguin canada ní ọdún 2012 ìwé yí ni ó gba amì-ẹ̀yẹ scotiabank giller prize ní ọdún 2012 àkòrí ìwé yí ni ó da lórí ìwà ọ̀daràn alọ́nilọ́wọ́gbà tí ìjọba orílẹ̀-èdè nàìjíríà ń gbógun tì ìwé yí ni ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀... |
ti oluwa ni ile 1993 film by tunde kelani ti oluwa ni ile jẹ́ eré oníṣe agbéléwò yorùbá tí alàgbà túndé kèlání darí rẹ̀ wọ́n gvé eré yí jáde ní ọdún 1993 lábẹ́ ilé-iṣẹ́ agbéré-jáde ti mainframe films and television productions eré yí ni ó gbé alàgbà túndé kèlání gẹ́gẹ́ bí adarí eré |
abọ́bakú abọ́bakú ni eré oníṣẹ́ agbéléwò kan tí femi odugbemi ṣe akọsílẹ̀ rẹ̀ tí niji àlàmú sì darí rẹ̀ bákan náà eré náà gba amì-ẹ̀yẹ most outstanding short film ní ibi ayẹyẹ zuma film festival àti best costume tí wọ́n ṣe ní ibi ayẹyẹ 6th africa movie academy awards ní ọdún 2010 àwọn ayẹyẹ yí ni wọ́n wáyé ní ìlú yenag... |
the narrow path the narrow path ni eré oníṣẹ́ tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2006 tí alàgbà túndé kèlání gbé jáde tí ó sì darí rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n ṣe àfàyọ eré yí láti inú ìwé onítàn the virgin ìwé tí bayo adebowale ke jáde agbékalẹ̀ eré náà eré yí ni ó sọ nípa ìṣòro tí ẹ̀dá ìtàn kan tí ó jẹ́ awẹ̀ró tí ó ní láti ... |
adigun nàìjíríà |
ibadan peoples party ipp ẹgbẹ́ ìṣèlúibadan peoples party ipp ni àwọn lààmì-laaka ọmọ bíbí ilẹ̀ ìbàdàn tí wọ́n tako bí nkan ṣe ń lọ ní apá ìjọba ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ yorùbá ṣe ń lọ sí wọ́n da ẹgbẹ́ ìṣèlú yí sílẹ̀ ní ọdún 1950s àwọn tí wọ́n jẹ́ abẹnugan inú ẹgbẹ́ náà ni augustus akinloye tí ó jẹ́ alága nígbà tí ọ̀pọ̀ nínú àwọ... |
owe yoruba òwe ni ohùn ìjìnlẹ̀ ẹnu àwọn àgbà-gbà ní ilẹ̀ yorùbá tí ó kun fún ọgbọ́n ìmọ̀ ìṣítí ìkìlọ̀ àti òye àwọn bàbá ńlá baba wa ní ilé káàrọ̀-o-kò- jíire àwọn àgbà-gbà yorùbá ma ń ṣe àmúlò òwe láti lè sọ́ra fún àsọjù tàbí àsọdùn ọ̀rọ̀ nígbà tí wọ́n bá wà ní àwùjọ tàbí wọ́n ń tàkurọ̀sọ pẹ̀lú ẹlòmíràn ọmọ yorùbá tí k... |
àsìá ilẹ̀ eswatini àsìá ilẹ̀ eswatini ni afrika |
flag of eswatini |
oduwacoin oduwacoin jẹ ilolupo sisanwo oni-nọmba ti a kọ lori ipilẹ alugoridimu pow / pos o nlo imọ-ẹrọ ẹlẹgbẹ-si-ẹgbẹ lati yanju gbogbo awọn iṣowo rẹ laarin nẹtiwọọki o jẹ abinibi akọkọ pure-pos cryptocurrency ti a ṣe ni ile afirika ipinle oduwacoin jẹ ilolupo eto isanwo oni-nọmba onijagidijagan ati ojutu fintech si i... |
t b jóṣúà |
tolulope arotile tolúlọpẹ́ olúwatóyìn sarah arótilé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kejìlá ọdún 19965 tí ó ṣaláìsí ní ọjọ́ọ́ kẹrìnlá oṣù keje ọdún 2020 tolúlọpẹ́ jẹ́ olùkọ́ ọkọ̀ òfurufú àwọn jagunjagun ní ilé iṣẹ́ ológun òfurufú ó sì tún jẹ́ obìnrin akọ́kọ́ tí yóò jẹ́ jagunjagun tí ó ń fi ọkọ̀ ìjà òfurufú jagun ní o... |
sope willams elegbe sope willams elegbe ti a bi ni 9 oṣu kẹjọ ọdun 1975 jẹ olukọ ọjọgbọn ti ofin ti ilu naijiria ọlọgbọn rira ni gbangba ati alatako iwa ibajẹ alagbawi ati agbọrọsọ fun ṣiṣakoso ṣiṣi silẹ iduroṣinṣin ati alatako ibajẹ ofin wto ofin idagbasoke sope jẹ alamọran fun awọn ijọba oriṣiriṣi banki agbaye ati pe... |
ijan ekiti ìjàn èkìtì jẹ́ ìlú ńlá kan tí ó wà ní ìpínlẹ̀ èkìtì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà iye àwọn olùgbé ibẹ̀ jẹ́ ọmọ yorùbá àtàtà tí wọ́n sì yan iṣẹ́ àgbẹ̀ láàyò gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ òòjọ́ wọn tí wọ́n sì ń gbin àwọn ohun ọ̀gbìn bíi ìrẹsì ẹ̀gẹ́ iṣu tábà òwú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ bá kan náà ni wọ́n yan iṣẹ́ aṣọ híhun láàyò gẹ́gẹ́ b... |
èrúwà èrúwà tàbí èrú wà níbí o ni ó túmọ̀ sí wípé ẹ̀rún iṣu wà ní ibí jẹ́ olú ìlú fún agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlà oòrùn ìbàràpá ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà èrúwà sí ìlú abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn tó kìlómítà ọgbọ́ta 60 km nígbà tí ó tó kìlómítà 72 km sí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ìtàn èrúwà ìlú èrúwà rí orúkọ ... |
àsìá ilẹ̀ galmudug àsìá ilẹ̀ galmudug ni afrika |
aso oke |
patrick bijou he sir patrick tristram bijou ti a bi ni oṣu kejila ọjọ 1 ọdun 1958 jẹ agbẹjọro ati onkọwe o jẹ adajọ fun international court of justice-international criminal court icj-icc ati ambassador fun world peace tracts sir patrick wa knighted ni ọdun 2018 nipasẹ aṣẹ ti awọn adari ọba ti ilu china ati ilu họngi k... |
achu achu jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ tó gbajúmọ̀ láàrin àwọn ara ́orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù ó jẹ́ oúnjẹ kan tí wọ́n maá n fi iyán kókò pèlòo rẹ̀ pẹ̀lú epo pupa pẹ̀lú pànmá àti àwọn èròjà mìíràn |
afang ọbẹ̀ ọbẹ̀ afang jẹ́ irúfẹ̀ ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ kan ti ilẹ̀ adúláwọ̀ èyí tí ó ṣẹ̀ wá láti ọ̀dọ̀ àwọn ìran efik ti ìpínlẹ̀ kàlàba àti àwọn ìran ibibio ti ìpínlẹ̀ akwá ibòm lórílẹ̀ èdè nàìjíríà |
ahriche ahriche ni oúnjẹ kan tó gbajúmọ̀ lórílẹ̀-èdè mòrókò ó sì wọ́pọ̀ láàrin àwọn ìran zayanes àti khénifra orúkọ oúnjẹ náà jẹyọ láti ibi pípèlò rè látàrí wípé ó pẹ̀lú fífi ìfun ẹran kọ́ sára igi léyìí tí wón ò tẹ̀ẹ́ sórí àrò |
alloco alloco jẹ́ ìpápánu ilẹ̀ adúláwọ̀ tí a máa ń jẹ pẹ̀lú ata gúngún àti alùbọ́sà ní orílẹ̀-èdè côte d'ivoire àti bọ̀kínà fasọ̀ òun náà ni a tún máa n pè ní dòdò èyí tó gbajúmọ̀ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà bákan náà àwọn ará kamẹrúùnù mọ̀ọ́ sí missolè bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ará ghánà a máa pèé ní kelewele wọ́n maá n pèlòo rẹ̀ pẹ̀... |
asida asida jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ tó gbajúmọ̀ láàrin àwọn lárúbáwá ti ilẹ̀ áfríkà wọ́n maá n pèlòo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti maá dáná òkèlè nígbà mìíràn wọn a máa sèé pẹ̀lú oyin tàbí bọ́tà |
attiéké attiéké jẹ́ ìpapánu tí a maá n ṣe látara ẹ̀gẹ́ èyí tí ó gbajúmọ̀ tó sì jẹ́ oúnjẹ àṣà orílẹ̀-èdè côte d'ivoire àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ní ìwọ-òrùn áfríkà |
baba ghanoush baba ghanoush jẹ́ oúnjẹ amébipanú kan tí wọ́n maá n pèlò ní ilẹ̀ lárúbáwá wọn a máa pẹ̀lo rẹ̀ pẹ̀lú èso ìgbá tí wọ́n ti gún àti àwọn orísirísi èrònjà mìíràn wọn a máa jẹ baba ghanoush pẹ̀lú àlùbọ́sà tàbí nígbà mìíràn pẹ̀lú ata tòmátò |
ọbẹ̀ banga ọbẹ̀ banga jẹ́ ọbẹ̀ kan tí wọń maá n pèlò látara èkùrọ́ táa fí n pèsè epo pupa ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn ìran urhobo ti ìpínlẹ̀ dẹ́ltà lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì gbajúmọ̀ káàkiri àwọn orílè-èdè mìíràn ní ilè adúláwọ̀ ìran akan ti orílẹ̀-èdè ghánà mòó sí abenkwan |
bazin bazin jẹ́ irúfẹ̀ búrẹ́dì tí àwọn ará orílè-èdè líbíyà maá n jẹ wọ́n maá n pèlo rẹ̀ pẹ̀lú ríro èlùbọ́ bálì lórí iná wọ́n sì maá n jẹẹ́ pẹ̀lú obẹ̀ tòmátò ẹyin òdùkú àti ẹran àgùntàn |
kiliṣi kílìṣi jẹ́ irúfẹ̀ ẹran ìpapánu tí ó ṣẹ̀ wá láti ẹ̀yà àwọn haúsá ó jẹ́ oríṣi ẹran tí wọ́n maá n gé sí pẹlẹbẹ tí wọ́n sì tún maá n sa sóòrùn lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n bá ti rìí bọ omi ata tí wọ́n ti pọ̀ mọ́ àwọn èrònjà mìíràn |
bobotie bobotie jẹ́ oúnjẹ tó ṣẹ̀ wá tó sì tún wọ́pọ̀ ní orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà wọn a máa pèlo rẹ̀ pẹ̀lú lílọ ẹran kúnná èyí tí wọn ó sè pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èrònjà títí yóó fi jinná dé ààrin kan lẹ́yìn náà wọn ó parí rẹ̀ pẹ̀lú dída ẹyin àti mílìkì si lórí |
boerewors boerewors jẹ́ oúnjẹ ti ilẹ̀ adúláwọ̀ tó gbajúmọ̀ ní apá gúúsù áfríkà wọn a máa pèlò rẹ̀ pẹ̀lú lílọ ẹran màlúù àti ti ẹlẹ́dẹ̀ àti ti àgùntàn èyí tí wọn ó ra róbóróbó síwáju kí wọ́n tó din nínú epo ó maá n pẹ̀lú oríṣiríṣi èrònjà wọ́n sì maá n fi mu ẹ̀kọ |
boerewors-roll boerewors-roll jẹ ẹya burẹdi ti wọn maa n fi boerewors eyi ti ati yaan daadaa si aarin meji rẹ o tun maa n pẹlu alubọsa lati fun ounjẹ naa ni adun to dara o gbajumọ ni orilẹ-ede guusu afrika ati awọn agbegbe rẹ |
brik brik jẹ́ oúnjẹ tó gbajúmọ̀ ní apá árèwá áfríkà pàápàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè tùnísíà ó jẹ́ ẹ̀yà oúnjẹ tí wọ́n maá n ṣe látara èròjà bíi èlùbọ́ ẹ̀gẹ́ ẹyin ẹja ata àti àwọn èròjà mìíràn |
briouat briouat jẹ́ oúnjẹ tó gbajúmọ̀ ní apá árèwá áfríkà pàápàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè mòrókò ó jẹ́ ẹ̀yà oúnjẹ tí wọ́n maá n ṣe látara èròjà bíi èlùbọ́ ẹ̀gẹ́ mílìkì ẹran ata àti àwọn èròjà mìíràn lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà oríṣi ẹran méjì tí wọ́n maá n sábàálò ni ẹran ẹdìyẹ tàbí ẹran àgùntàn |
bunny chow bunny chow jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ tó gbajúmọ̀ ní apá gúúsù áfríkà pàápàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà fúnrarẹ̀ ó jẹ́ irúfẹ̀ oúnjẹ kan tí wọ́n maá n pèlò pẹ̀lú yíyọ ihò sáàrin búrédì láti lè da ọbẹ̀ ẹran tàbí ọbẹ̀ mìíràn sáàrin búrẹ́dì náà ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn ìran índíàn tí wọ́n fi ìlu dúrbàn ní orílẹ̀-è... |
chakalaka chakalaka jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ tó gbajúmọ̀ ní apá gúúsù áfríkà pàápàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà fúnrarẹ̀ àti sìmbábúè ó jẹ́ irúfẹ̀ oúnjẹ kan tí wọn kò kí n dájẹ lóun nìkan àyàfi kí wọ́n fi jẹ búrẹ́dì tàbí mu ẹ̀kọ ó wọ́pọ̀ ní ìlu johannesburg ní orílẹ̀-èdè gúúsù áfríkà |
chermoula chermoula jẹ́ èròjà oúnjẹ tí wọ́n maá n pèlò ní ilẹ̀ adúláwọ̀ èyí tó gbajúmọ̀ ní apá árèwá áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè bíi àlgéríà líbyà mòrókò àti tùnísíà wọ́n maá n lòó láti lékún aadùn oúnjẹ |
ilu osu osu jẹ ilu ti o wa ni iwọ-oorun ti ipinle osun ni iwọ-oorun iwọ-oorun najiiria ipo osu wa ni agbegbe ijoba ibile atakumosa-west ti ipinle osun ipinle osun jẹ apakan ti agbegbe ndagba koko ti ndagba ni iwọ-oorun lẹhinna o ti jẹ opin irin-ajo pataki fun awọn agbe agbe lati awọn ẹya miiran ti nigeria aje osu jẹ oh... |
okeho okeho jẹ ilu ti o wa ni kajola ipinle iwọ-oorun nigeria o jẹ olu-ilu kajolao je olu ilu kajola ipo o jẹ ilu afonifoji ati agbegbe igberiko kekere ni awọn ẹhin ẹhin ti ipinle oyo awon oke-nla ati awọn afonifoji yi ilu ka awọn ilu bii ilero ilua ayetoro-oke isemi ile iwere-oke ilaji-oke yi kaari ilu afonifoji kan t... |
temi dee tèmídayọ̀ adébanjọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ jùlọ sí temi dee jẹ́ akọrin àti ònkọ̀wé ọmọ orílè-èd̀e nàìjíríà ibere aye ati iṣẹ orin re a bí temi dee ní ìpínlẹ̀ èkóní orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun àti ẹbí rẹ̀ kó lọ sí ìlú london nígbà tí ó wà ní èwe temi dee bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní ọdún 2014 ó gbé àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jád... |
otan ayegbaju ọ̀tan ayégbajú òtan tabi ọ̀tan kòtò gege bi won se n pe ni igba iwase jẹ́ ìlú ìtàn ní ilẹ̀ yorùbá tí wọ́n jẹ́ ọmọ bíbí odùduwà tí wọ́n wá láti ilé-ifẹ̀ ní nkan bí ọdún 500 sẹ́yìnó jẹ̣́ olú-ìlú tí ó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ boluwaduro àwọn ìlú tí ó wà nítòsí rẹ̀ ni eripa ìrẹ̀sì ìgbájọ òkè-run àti ọ̀yan ọ... |
dufuna canoe dufuna canoe jẹ́ ọkọ̀ ojú-omi kékeré kan tí a ṣe àwárí i rẹ̀ ní ọdún 1987 látipasẹ̀ fulani darandaran màálù kan ní ibùsọ̀ díẹ̀ si abúlé ti dufuna ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ fune èyí tí kò jìnnà sí odò komadugu gana ni ipinle yobe orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbáraẹnisọ̀rọ̀ radiocarbon ti àpẹẹrẹ èédú tí wọ́n ṣe àwárí... |
temilade ọpeniyi |
taiwo kola-ogunlade taiwo kola-ogunlade jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ní ìmọ̀ nípa ìbáraẹnisọ̀rọ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ oun ni olùṣàkóso ti ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọ̀rọ̀ ìlú fún ilé iṣẹ́ ayélujára google ti ìla òòrùn áfíríkà iṣẹ́ kọ́lá-ògúnlàdé gba oyè láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga yunifásítì ìpínlẹ̀ èkó ní nàìjíríà lórí i bio... |
àrùn òtútù |
onitsha market ọjà onitsha tí a tún mọ̀ ní ọjà onitsha àkọ́kọ́ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọjà tí ó tóbi júlọ ní ìwọ̀-òòrù áfíríkà èyí tí ó dá lóríi bí ó ti tóbi tó àti oríṣiríṣi ọjà tí ó wà níbẹ̀ ọjà yí fìdí kalẹ̀ sí ìlú onitsha olú-ìlú ìṣòwò ti ìpínlẹ̀ anámbra ní gúúsù ìla-òòrùn naijiria ẹgbẹ́ oníṣòwò ọjà onitsha tí àdàpè rẹ... |
saginaw grant saginaw morgan grant july 20 1936 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
ọjà ẹrù veléketé velekete ọjà ẹrú ni ọjà ará tí ó wà ní ìlú àgbádárìgì ní ìpínlẹ̀ èkó wọ́n da ọjà òwò ẹrú yí sílẹ̀ ní ọdún 1502 wọ́n sọ orúkọ ọjà yí ní velekete tí ó jẹ́ orúkọ òrìṣà omi ati afẹ́fẹ́ọjà yí gbajúmọ̀ gidi ní àsìkò owó ẹrú káàkiri trans-atlantic slave trade ó sì tún jẹ́ ojúkojú tí àwọn abáni rẹrú ti ma ń dú... |
àtòjọ àwọn pápákọ̀ òfurufú ilẹ̀ china èyí ni àtòjọ àwọn pápákọ̀ òfurufú tí wọ́n wà fún àwọn ìlò gbogbo àwùjọ ní orílẹ̀-èdè china pẹ̀lú ìpínsísọ̀rí wọn pẹ̀lú ìlú tí wọ́n wà lára àwọn ọkọ̀ òfurufú náà ni àwọn èyí tí wọ́n ti ṣe tán tàbí àwọn èyí tí wọ́n ṣe lọ́wọ́àmọ́ kò sí àwọn èyí tí wọ́n ti di àlòpatì níbẹ̀ military air... |
ọjà kurmi ọjà kurmi jẹ́ ọjà tí ó tóbi tí ó wà ní ìlú kano ní ipinle kano orile-èdè nàìjíríà muhammad rumfa ẹnití ó jẹ́ ọba kano ni ó dá ọjà yí sílẹ́ ní ọ̀rúndún kẹẹ̀dógún ọjà yí ṣì tún wà ní lílò ní ọ̀rúndún kọkánlélógún títí di ọdún 2003 sale ayagi ní ó jẹ́ alága ẹgbẹ́ àwọn ọlọ́já orúkọ ẹgbẹ́ àwọn agbá bọ̀ọ̀lù kan ni ... |
mandy patinkin mandel bruce patinkin november 30 1952 je osere ara amerika |
karakalpakstan karakalpakstan onibise bi orile-ede olominira aladawa ile karakalpakstan qoraqalpog'iston avtonom respublikasi je orile-ede olominira aladawa ile ùsbẹ̀kìstán |
list of railway lines in china àtòjọ àwọn ojú ọ̀nà rélùwéè ní orịlẹ̀-èdè china rail transport in china láti mọ̀ nípa àwọn tí wọ́n yára jùlọ ẹ wo the high-speed network ẹ sì lè wo àwọn tí wọ́n ń lo iná mọ̀nà-mọ́ná list of high-speed railway lines in china èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ láti ẹkùn àríwá-gúsù apá beijing-harbin lára àwọn... |
chinese tea boilerplate seealso>ẹ tún wo chinese tea culture tiì ilè china ni ohun mímu tí wọ́n pèsè láti ara ewé tì orúkọ rẹ ń jẹ́ camellia sinensis àti omi gbígbóná wọ́n ma ń se tíì yí ní ìlànà ìbílẹ̀ ní ṣáínà tíì china ni a lè mu ní gbogbo ìgbà tàbí àsìkò tí ó bá wù wá lójúmọ́ kódà a lè ma mú dípò omi tí a ń mu ní g... |
kunqu kunqu tí a tún mọ̀ sí kunju k'un-ch'ü kun opera tàbí kunqu opera jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin ìbílẹ̀ ìgbàanì tí àwọn china ó jẹ́ ẹ̀yà orin ìbílẹ̀ china tí ó yà láti ara orin kunshan tí ó sìn wá di gbajúmọ̀ nínú àwọn eré-oníṣe tí àwọn china láti nǹkan bí i sẹ́ńtúrì 16 sí 18 ẹ̀yà orin yìí ṣẹ̀ láti inú àṣà àwọn ẹ̀yà wu ... |
àjọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá china àjọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá china the chinese football association cfa jẹ́ àjọ ẹgbẹ́ tí wọ́n ń darí eré bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá eré bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí etí òkun àti eré bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá orí àpáta tí orílẹ̀ èdè china ní mainland china wọ́n dá àjọ yìí sílẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ní beiji... |
yu xu yu xu tí wọ́n bí lóṣù kẹta ọdún 1986 ó sìn ṣaláìsí lọ́jọ́ kejìlá oṣù kọkànlá ọdún 2016 jẹ́ ọmọgun-bìnrin adarí àwọn awakọ̀ òfuurufú ọmọ orílẹ̀-èdè china tí ó dárí ẹgbẹ́ àwọn ọmọ ẹ̀kọ́ṣẹ́ ọkọ̀ òfuurufú tí wọ́n ń pè ní august 1st aerobatic team tí àwọn ọmọ-ogun people's liberation army air force ìgbà èwe rẹ̀ wọ́n b... |
list of ports in china orílẹ̀-èdè china ní èbúté ọkọ̀ ojú-omi tí ó jẹ́ gbogbo gbo tí ó tó mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n nígbà tí wọ́n ní àwọn èbúté kéréje-kéréje tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún méjì lápapọ̀ yàtọ̀ sí àwọn èbúté tí wọ́n jẹ́ gbajú-gbajà bíshanghai nanjing ati nantong pẹ̀lú along èbúté yangtze ati guangzhou tí wọ́n wà ní ìtòsí odò... |
àjọ alákòóso fún rélùwéè ilẹ̀ china àjọ alákòóso fún rélùwéè ilẹ̀ china mor ni ilé-iṣẹ́ tí ó wà ní abẹ́ state council of the people's republic of china amọ́ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́ ẹni tí ó jẹ́ mínísítà kẹyìn fún àjọ yí ni sheng guangzu ojúṣe àjọ yí ni kí wọ́n ṣe àbójútó lílọ bíbọ̀ èrò ọkọ̀ láì sí ìdíwọ́ kan kan ṣiṣẹ́ ètò ati ... |
àtòjọ orúkọ àwọn ọmọ orílẹ̀ - èdè amẹ́ríkà tí orírun wọn jẹ́ china èyí ni àtòjọ orúkọ àwọn ènìyàn pàtàkì tí wọ́n jẹ́ ọmọ amẹ́ríkà ṣùgbọ́n tí orírun wọn jẹ́ china àwọn orúkọ wọ̀nyí jẹ́ ti àwọn tí wọ́n kọjá sí amẹ́ríkà fún ara wọn tàbí àwọn ọmọ amẹ́ríkà ṣùgbọ́n tí ìran wọn jẹ ti china tí wọ́n sìn tí ṣe nǹkan pàtàkì láwùj... |
yunifásítì ìlú paris-saclay yunifásítì ìlú paris-saclay tabi yunifasiti paris-saclay jẹ́ yunifásítì kan ní ìlú gif-sur-yvette fránsì upsa ti wa ni àìyẹsẹ ni ipo ninu awọn ti o dara ju egbelegbe ni aye lati oṣu kẹwa ọdun 2023 ile-ẹkọ giga ti jẹ alabaṣepọ ti ipsa fun awọn iwọn meji ni oju-ofurufu |
université paris-saclay |
xu qing xu qing tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún oṣù kìíní ọdún 1969 tí a tún mọ̀ sí summer qing jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ china wọ́n gbà á sí ilé-ẹ̀kọ́ sinimá beijing film academy lọ́dún 1988 ó sìn kẹ́kọ̀ọ́ jáde lọ́dún 1992 iṣẹ́ ọdún 1999 ni xu kọ́kọ́ jáde nínú sinimá kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ made life on a string tí ch... |
china state shipbuilding coorporation àwọn ilé-iṣẹ́ ìpínlẹ̀ china tí wọ́n ṣe ọkọ̀ ojú-omi akérò ní ilẹ̀ china tí a mọ̀ sí cssc ni ó jẹ́ ilé iṣẹ́ aláfọwọ́ sowọ́pọ̀ tí wọ́n ń kọ́ ọkọ̀ ojú-omi akérò ní ilẹ̀ china agbékalẹ̀ rẹ̀ cssc ni ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn ẹ̀ka mẹ́wàá nílé iṣẹ́ ọmọ ogun ní orílẹ̀-èdè china ni ó ní ... |
list of chinese administrative divisions by illiteracy rate gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn the sixth population census ẹlẹ́kẹfà irú rẹ̀ ti sọ ní ọdún 2010 àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n kàwé ní irílẹ̀-èdè chinajè 959 amọ́ iye àwọn tí wọ́n kàwé ní ẹkùn-ò-jẹkùn ni wọ́n yá tó síra wọn àwọn eléyí ni wọ́n wà ní ìpele anọ́kọ́ nínú ì... |
àtòjọ àwọn oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ounje adulawo |
project 211 project 211 ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1995 tí ó jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe tí óbdá lórí àwọ fásitì tí wọ́n ṣe pàtàkì ní orílẹ̀-èdè china lábẹ́ àjọ tí ó bójútó ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́lé wọ́n da iṣẹ́ àkànṣe yí sílẹ̀ láti lè fi ẹsẹ̀ iṣẹ́ ìwádí tó peregedé múlẹ̀ kí wọ́n sì wá àwọn ọ̀nà tó yanrantí fún ìdàgbà-sókè àwùjọ nígbà tí wọ́n... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.