raw_text
stringlengths
2
128k
ìlèdí absorbent item worn in the underwear by women who are menstruating bleeding after giving birth or similar ìlèdí fún ọmọdé ìlèdí tàbí ìlàpọ̀n fún àgbà tàbí páàdì fún àwọn obìnrin jẹ́ ohun èlò kan tí ó ma ń gba omi bíi ìtọ̀ àti ìgbẹ́ ènìyàn dúró lára ọmọ ìkókó tàbí ọmọdé ó tún jẹ́ ohun èlò tí àwọn obìnrin ma ń lò l...
nkan oṣù ṣíṣàn jáde ẹ̀jẹ̀ lóòrè kóòrè láti ojú ara àwọn obìnrin tí wọ́n ti bàlágà láti inú òbò wọn nkan oṣù tí a tún mọ̀ sí àlejò obìnrin jẹ́ ṣíṣàn jáde papọ̀ ẹ̀jẹ̀ àti ikun tí a ń dà pè ní nkan oṣù ni ónma ń jáde láti inú àpò-lùkẹ́ tabí ilé-ọmọ obìnrin gba inú òbò jáde nkan oṣù àkọ́kọ́ sábà ma ń bẹ̀rẹ̀ lára ọmọdé tí ó...
narendra modi narendrabhai damodardas modi ni mínísítà àgbà india kẹrìnlá àti mínísítà àgbà tí india lọ́wọ́ lọ́wọ́ lati ọdun 2014 o jẹ oloselu kan lati bharatiya janata party agbari-iṣẹ oluyọọda ara ilu hindu kan oun ni prime minister akọkọ ni ita ti ile-igbimọjọ ti orilẹ-ede india lati ṣẹgun awọn ofin itẹlera meji pẹl...
jaekel house ilé jaekel jẹ́ ilé alájà méjì òyìnbó àmúnisìn tí ó wà ní ìlú èbúté mẹ́ta ní ìpínlẹ̀ èkó wọ́n kọ́ ilé náà ní ọdún 1898 sí orí ilẹ̀ tí ó pò kan tí wọ́n sì sọ ilé náà ní orúkọ olóògbé francis jaekel obe tí ó jẹ́ alámòójútó àgbà fún ilé-iṣẹ́ rélùwéè ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó fẹ̀yìn tì ní ọdún 1970 ilé ilé ja...
broad street broad street jẹ́ òpópónà kan tí ó wà ní lagos island tí ó wà ní ìpínlẹ̀ èkó òpópónà yí jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn pópó tí àwọn ọlọ́jà ti ń taja jùlọlára àwọn ilé ìtajà tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ni bagatelle restaurant ilé-ẹ̀kọ́ christ church cathedral primary schoolilé-ẹ̀kọ́ eko boys high school ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròy...
ọbáléndé obálendé ni ó túmọ̀ sí ibi tí ọba lé wa dé jẹ́ àdúgbò kan tí ó wà ní àárín ìlú èkó ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ etí-ọ̀sà tí ó súnmọ́ lagos island etí-ọ̀sà yí ni ìjọba ìpínlẹ̀ èkó pín sí abẹ́ ìjọba ìbílẹ́ onídagbà-sókè èyí tí ìkòyí- ọbáléndé wà nínú rẹ̀ ọbáléndé ni ó ní àwọn ilé-ẹ́kò bíi holy child college ọbáléndé ...
abeokuta women's revolt
razia sultan sinimá àgbéléwò razia sultan jẹ́ sinimá àgbéléwò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán onípele tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ ajé sí ọjọ́ etì lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán tv láti ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 2015 pankhuri awasthy ni ó kópa olú ẹ̀dá ìtàn náà tí ó ń jẹ́ razia sultana eré-oníṣe náà dá lórí razia sultan sultan ra...
òkè-ìmẹ̀sí ìlú òkè-ìmẹ̀sí jẹ́ ìlú kan lára awọn ìlú tí ó korajọ pọ̀ di ìjọba ìbílẹ̀ ìwọ oòrùn èkìtì lga ní ìpínlẹ̀ èkìtì wọ́n fi léde wípé iye àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbé ìlú náà jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n 30000 bí ó ṣe tó ìlú òké-ìmẹ̀sí wa ní ìpínlẹ̀ èkìtì ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà òké-ìmẹ̀sí tó 782° ìbú ní ap...
ẹ̀yà hausa eya awusa ni eya kan laarin awon eya orilede naijiria
peter new peter new october 30 1971 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà
clarius ugwuoha clarius ugwuoha jẹ onkọwe ilu naijiria o kọ awọn ewi prose ati awọn ewi o jẹ akọọlẹ atokọ blooker ni 2006
alfred freddy krupa
ìlú ọ̀tà ìlú ọ̀tà tì á tún mọ̀ sí otta jẹ́ ílú kán nì ìpínlé ogún ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àtí pé o ní iye àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbéré-jáde tí ó tó 163783 ń iye ọ̀tà ni ó ìlú tí ìjọba ìbílẹ̀ adó-odò wà ọba alaye àti aláṣẹ tí ó wà lórí àga àṣẹ lọ́wọ́ lọ́wọ́ yí ni ọ́lọ̀tá tí ọ́tá ọba adéyẹmí abdulkabir ọba lánlẹ́gẹ́ g...
doyin okupe adédoyin ajíbíkẹ́ òkúpè tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹ́ta ọdún 1952 tí a tún mọ̀ sí dokita doyin òkúpè jẹ́ dókítà àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̣̀-èdè nàìjíríà kan ti o ṣe agbekalẹ ile-iṣẹ ipoogun ti royal cross pe o jẹ akọwe ikede ti orilẹ-ede ti national republican convention nrc ó wà lára àwọn tí ọ̀gágun sani...
jaswant singh major jaswant singh 3 oṣu kini ọdun 1938 - 27 oṣu kẹsan 2020 jẹ oṣiṣẹ ti ọmọ ogun india ati minisita fun igbimọ india o jẹ ọkan ninu awọn ọmọ ẹgbẹ ti o da silẹ ti bharatiya janata party bjp
oṣù kẹ̀wá
oṣù ọpẹ
oṣù belu
oṣù ọwẹ́wẹ̀
oṣù owàrà
oṣù ògún
oṣù agẹmọ
oṣù okúdù
oṣù èbìbí
oṣù igbe
oṣù ẹrẹ́nà
oṣù èrèlé
oṣù ṣẹ́rẹ́
1 oṣù ṣẹ́rẹ́
wayne brady wayne alphonso brady june 2 1972 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà
ọ́ta ogun
rajput caste ri ni awọn orilẹ-ede guusu-esia rajput lati sanskrit raja-putra ọmọ ọba kan jẹ iṣupọ paati pupọ ti awọn olukọ awọn ara ibatan ati awọn ẹgbẹ agbegbe pinpin ipo awujọ ati arojinlẹ ti idile iran ti o bẹrẹ lati oro naa rajput ti gba itumọ rẹ ni bayi ni ọdun kẹrindilogun botilẹjẹpe o tun lo anachronistically la...
òrìṣábùnmi fọlákẹ́ àrẹ̀mú tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí òrìṣàbùnmi tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1960 tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹfà oṣù kìíní ọdún 2021 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti eléré orí ìtàgé ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ kwara lórílẹ̀-èdè nàìjíríà
ìjọba ìbílẹ̀ obòkun 'obòkun jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ilé ìjọba ìbílẹ̀ rẹ̀ wà ní ibòkun at ìjọba ìbílẹ̀ obòkun ní ilé tí ó tó 527 km2 tí àwọn olùgbé ibẹ̀ lápapọ̀ sì tó 116511 níye gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ṣe fi lélẹ̀ nọ́mbà ìlà ìpè tí ó ja sí agbègbè naa ni 233 lára àwọn ìl...
ìlú bàsà bassa jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní abẹ́ akóso ìjọba ìbílẹ̀ ogunma ní ìpínlẹ̀ kogí ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìlú yí pààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ benue ní apá gúsù ó pààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ niger ní apá ìwọ̀-oòrùn ìlú bàsà ní ìlẹ̀ tí ó tó 1925 km2 níye wọ́n sì ní àwọn olùgbé tí wọ́n ń gbé níbẹ̀ 139993 gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006...
ọlábísí ọnàbánjọ olóyè victor ọlábísí ọnàbánjọ ni wón bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì ọduń 1927 tí ó sì papò dà ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin ọdún 1990 jẹ́ gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní ìpínlẹ̀ ògùn ní àárín ọdún 1979 sí ọdún 1983 ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà ayé òṣèlú ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà he was of ijebu extraction ìgbé ayé r...
olú abọ́dẹrìn olú abọ́dẹrìn tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹta oṣù kẹsàn-án ọdún 1934ti oó sìn kú lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1984 jẹ́ gbajúmọ̀ olóòtú ìwé-ìròyìn ọmọ nàìjíríà tí ó wà lára àwọn tí wọ́n dá ìwé-ìròyìn the punch sílẹ̀ ó fìgbà kan jẹ́ ààrẹ àwọn olùdásílẹ̀ ìwé-ìròyìn kí ó tó kú lọ́dún 1984 bẹ́ẹ̀ náà ó jẹ́ ògnóǹ...
olóyè bísí ọnàbánjọ
ìbàdàn grammar school secondary school in nigeria ìbàdàn grammar school ni ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ girama kan tí ó wà ní agbègbè mọ̀lété ní ìgboro ìlú ìbàdàn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìtàn bí wọ́n ṣe da sílẹ̀ wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1913 ilé-ẹ̀kọ́ yí jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tí...
the punch the punch jẹ́ ìwé ìròyìn ojoojúmọ́ ti orílẹ-èdè nàìjíríà tí ó dá ní oṣù kẹjọ ọjọ́ 8 ọdún 1970 punch nigeria limited ti forúkọsílẹ̀ lábẹ́ òfin àwọn ilé-iṣẹ́ ti ọdún 1968 láti ṣe ìṣòwò titẹjade àwọn ìwé ìròyìn àti àwọn ìwé ìròyìn ìgbà kọ̀ọ̀kan ó jẹ́ àpẹrẹ láti sọ fún kọ́ ẹ̀kọ́ àti ṣe eré àwọn ọmọ nàìjíríà àti à...
àtòjọ àwọn ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde ní nàìjíríà àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde ní nàìjíríà wọ́n jẹ́ àwọn ìwé-ìròyìn tó gbajúmọ̀ tí wọ́n sìn kárí gbogbo orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń tẹ̀ jáde gẹ́gẹ́ bí ìwé àti àwọn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde lórí ìkànnì ayélujára ní nàìjíríà
àtòjọ àwọn oníròyìn àhesọ ìkànnì ayélujára èyí ni àtòjọ àwọn oníròyìn àhesọ ìkànnì ayélujára tó gbajúmọ̀ jùlọ ní nàìjíríà
ìwé ìròyìn ìwé ìròyìn gẹ́gẹ́ bí orúkọ rè ni ìwé àtẹ̀jáde olójoojúmọ́ tí wọ́n fi ma ń kọ tàbí sọ nípa ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ lọ́wọ́ tàbí ohun tí ó ń lọ nínú àwùjọ kan ìwé ìròyìn ma ń sábà sọ̀rọ̀ nípa oríṣiríṣi bí ọ̀rọ̀ ìṣèlú okòwò eré ìdárayá iṣẹ́ ọnà ìmọ̀ sạ́yẹ́nsì ọ̀rọ̀ nípa ojú ọjọ́ ìkéde ayẹyẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ b...
strawberry prince strawberry prince すとぷり sutopuri je ẹgbẹ orin ọkunrin japan awọn ọmọ ẹgbẹ mẹfa wa ninu ẹgbẹ naa nanamori jel satomi root rinu ati colon
baptist academy baptist academy jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ girama kan tí ó wà ní agbègbè ọbaníkòró ní ìpínlẹ̀ èkó àwọ́n ajíyìnrere ará ilẹ̀ amẹ́tíkà kan ni wọ́n wá dá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ sí ìlú èkó ní ọdún 1855 ilé-ẹ̀kọ́ yí jẹ́ ẹ̀ka ilé-ẹ̀kọ́ reagan memorial baptist girls' secondary school tí ó wà ní agbègbè yábá ní ìpínlẹ̀ èkó ìtà...
iwọ xie iwọ xie 謝盛友 ti a bi ni oṣu kẹwa ọjọ 1 ọdun 1958 ni hainan china jẹ oloselu ara ilu jamani kan oludije fun idibo ile igbimọ aṣofin european 2019 onise iroyin ati onkọwe abinibi ilu ṣaina
2021 <ns>10</ns> <id>10717</id> <revision> <id>160243</id> <parentid>157824</parentid> <timestamp>2011-01-04t164512z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ọ̀rúndún | ọ̀rúndún 210k ◄◄ | | | 2021 ọdún 2021 ọdún ẹgbàà ó lé móka...
sylvester madu sylvester madu tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kìíní ọdún 1975 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ anambra lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbà èwe rẹ̀ sylvester jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ anambra ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ fún ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama kí ó tó kàwé gboyè ní university...
àbò àbò jẹ ọrọ ti ede yourba rẹ
adémọ́lá adébise nigerian bank executive adémọ́lá adébise ni ó jẹ́ adarí àgbà àti olóòtú àgbà yán yán fún ilé-ìfowópamọ́ wema bank plc ìgbà èwe rẹ̀ wọ́n bí adébísí ní wọ́n bí ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1966 ní ìpínlẹ̀ èkó sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni àti arabìnrin adégòkè adébíse ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ baptist academy tí ó wà...
sunday ìgbòho olóyè sunday ìgbòho tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ sunday adéníyì adéyẹmọ tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1972 jẹ́ gbajúmọ̀ ajìjàǹgbara olóṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ajìjàǹgbara fún ìdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè oòduà àti ìṣọ̀kan àwọn ọmọ yorùbá káàkiri...
ṣiyan oyeweso
electricity sector in nigeria ẹka ina ni nigeria n gbejade tan kaakiri ati pinpin awọn megawatts ti agbara ina eleyi ti o dinku ni pataki ju ohun ti o nilo lati pade awọn ipilẹ ile ati awọn aini ile-iṣẹ ni ọdun 2012 ile-iṣẹ ṣiṣẹ lati pin awọn megawatt 5000 pupọ ti o kere si 40000 megawatts ti o nilo lati ṣe atilẹyin aw...
richard akínwándé savage richard akínwándé savage tí wọ́n bí ní ọdún 1874 tí ó ṣaláìsí ní ọdún 1935 ni ó jẹ́ òkan lára àwọn ògúná-gbòngbò onímọ̀ ìṣègùn oníṣẹ́ ìròyìn àti olóṣèlú ní àárín ìpínlẹ̀ èkó ní àsìkò ìjọba amúnisìn gẹ̀ẹ́sì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbà èwe rẹ̀ wọ́n bí richard ní ọdún 1874 sí ìdílé oníṣòwò kan tí ...
chris olukolade chris olukolade tí a bì ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 1959 jẹ́ ọ̀gágun àgbà tí ó jẹ́ agbẹnusọ fún ológun nàìjíríà tí ó ti fẹ̀yìn tì òhun ni wọ́n yàn lẹ́yìn tí ọ̀gágun brig gen mohammed yerima pàrí sáà rẹ̀ wọ́n sí yàn ọ̀gágun colonel rabe abubakar lẹ́yìn tí òhun náà parí sáà rẹ̀ bákan náà kí ó tó fẹ...
fela sowande
nika melia nikanor nika anzoris dze melia ojoibi 21 december 1979 je ara orile-ede georgia oloselu
billy connolly william billy connolly november 24 1942 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà
ìmàle
ilé kòkó ilé kòkó tí wọ́n kọ́ ní ọdún 1965 tí gíga tó ẹsẹ bàtà mítà márùnlé-lógọ́rún jẹ́ ilé tí ó ga jùlọ ní iwọ̀ oòru afíríkà dùgbẹ̀ ní iìlú ibadan ni ìpínle ọ̀yọ́ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni wọ́n kọ sí èrè owò ọ̀gbìn bíi kòkó rọ́bà igi ti ìpínle ìwọ̀-oòrún ti orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni wọ́n sì fí kọ́ ọ́ orúkọ àkọ́kọ́ tí wọ̣́n...
cocoa house
pólàndì
ọ̀rọ̀ àgbẹ̀
kọ́nsónántì èdè yorùbá kọ́ńsónáǹtì yorùbá ni ìró kọ́ńsónáǹtì ni ìró tí a pè tí ìdíwọ́ wà fún afẹ́fẹ́ tàbi èémí nínú káà-ẹnu kọ́ńsónáǹtì méjìdínlógún ló wà lédè yorùbá àpẹẹrẹ kọ́nsónántì èdè yorùbá ni b d f g gb h j k l m n p r s ṣ t w àti y ìlò kọ́nsónántì nínú èdè yorùbá kọ́nsónántì kìí dá dúró ba kan náà ni we kìí b ...
radio lagos radio lagos 1075 fm tí a tún mo sí tiwa n' tiwa ni ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní pẹrẹu ní ọdún 1977 ni ó jẹ́ ẹ̀ka ti nigerian broadcasting corporation ilé-iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì yí jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ ti ìpínlẹ̀ lórí ìkanì fm ilé-iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbésì yí ń gbòhùn sáfẹ́fẹ́ lórí ìkànì am méjì 990 khz303mtrs ...
british royal family idile ọba ilu gẹẹsi ni queen elizabeth ii ati awọn ibatan rẹ ko si ofin ti o muna tabi itumọ t’ọlaju ti tani tabi kii ṣe ọmọ ẹgbẹ ti idile ọba gẹẹsi ọpọlọpọ awọn ọmọ ẹgbẹ ṣe atilẹyin ayaba ni ṣiṣe awọn adehun gbangba ati nigbagbogbo lepa iṣẹ alanu ati awọn ifẹ wọn ṣe akiyesi idile ọba bi awọn aami ...
èébì èébì tí a tún mọ̀ sí ebi tàbí èbìbì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ni kí ikùn tàbí inú ẹni ó ma ru bàlà nígbà tí àwọn ohun tí a ti ja tàbí mu sínú ń gba ẹnu tàbí imú jáde síta pẹ̀lú agbara oríṣiríṣi nka ni ó lè fàá kíènìyàn ó ma bì lára rẹ̀ ni inú kíkún tí ó túmọ̀ sí wípé óúnjẹ kò dà nínú ènìyàn ohun mìíràn tí ó tún lè ṣokùnf...
àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríru àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríru htn tàbí ht a tún lè pè ní ẹ̀jẹ̀ gbígbóná tàbí hbp ni ó jẹ́ àìsàn tí ó ma ń lọ tí ó ń bọ̀ nínú àgọ́ ara fún ìgbà pípẹ́ nígbà tí ẹ̀jẹ̀ inú iṣan ọkàn ń lọ tàbí ru sókèju bí ó ti yẹ lọ ní gbogbo ìgbà ẹ̀jẹ̀ ríru kìí sábà ń fúni ní àmì kí ó tó bẹ̀rẹ̀ bí ẹ̀jẹ̀ ríru bá ṣe pẹ́ sí nínú ara ni ó...
noimot salako-oyedele nòímòt sàlàkó -oyèdélé jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ olósèlú onímọ̀ nípa ohun ìní omo bíbí orílẹ̀ èdè nàíjírìa ti a bí ní ọdún 1967bàbá rẹ̀ lateef a salako nnom con jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ẹ̀kọ́ àwọn òògùn àti olùkọ́ ni fásitì ilẹ̀ ìbàdàn ó jẹ́ igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ ògùn orílẹ̀ èdè nàijiria ó di ig...
rosé roseanne park je olorin omo orile-ede kòréà gúúsù
osai ejigho nigerian lawyer and human rights activist osai ojigho tí wọ́n bí ní ọdún 1976 jẹ́ ògbójú ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn amòfin àti oni kò-kárí ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni títí di 2021 update adarí àgbà fún ajọ amnesty international's fún orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tún ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí olùbádámòràn pàtà...
yejide kilanko nigerian canadian fiction writer and social worker yéjídé kílàńkó tí wọ́n bí ní ọdún 1975 ni omọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n sí orílẹ̀-èdè canada jẹ́ oniọ̀tàn ati oníṣẹ́ àwùjọ ó di gbajúmọ̀ nípasẹ̀ bí ó ṣe ma ń pẹ̀tù sí aáwọ̀ tí ó bá ti kan àwọn obinrin ìwé rẹ̀ tí ó kọ tí ó sọ ọ́ di ìlú-mòọ́ká ni daughte...
kikelomo longe kíkẹ́lọmọ longẹ ni kọmíṣánna fún oko-owo àti ile iṣẹ́ ni akoko yii ní ipinle ogun ìbẹ̀rẹ̀ igbesi ayé àti ẹ̀kọ́ kíkẹ́lọmọ longẹ jẹ́ ọmọ bíbí ìjọba ibilẹ gusu abeokuta ó kẹkọ nipa isiro owo ni ile ẹkọ giga yunifasiti ìlú eko ó si di komiṣana fun oko-owo ati ile iṣẹ ni ipinlẹ ogun nigbati gomina dapo abiodu...
ladi kwali ladi kwali oon mbe c1925 august 12 1984 jẹ́ amọ̀kòkò àti onímọ̀ nípa ẹ̀kọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ladi kwali ni wọ́n bí ní abúlé kan tí ó ń jẹ́ kwali ni agbègbè gbwari ní apá òkè ọyà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìlú tí ìkòkò ṣíṣe ti jẹ́ iṣẹ́ òójọ́ fún àwọn obìrin wọn ladi kọ́ bí wọ́n ṣe ń mọ ìkòkò láti ìgbà tí ó ...
kíkẹ́lọmọ longẹ
guillermo lasso guillermo lasso je aare orile-ede ekuador tele
lenín moreno lenín moreno je aare orile-ede ekuador tele
ejò ejò lápapọ̀ jẹ́ ẹranko gúngùn afàyàfà ri ó sì jẹ́ ọ̀kan lara àwọn ẹranko elégungun amọ́ tí egungun wọn kò lágbára wọ́n sì tún j ẹ́ ẹranko tí ó lè jẹ ẹranko ẹgbẹ́ wọn púpọ̀ nínú àwọn ẹ̀yà ejò ni wọ́n ní agbárí àti àwọn oríkèé-ríkèé ara ju alángbá lọ èyí ni ó fún wọn ní ànfaní láti lè gbé àwọn ẹranko ẹgbẹ́ wọn mì pàá...
kídìnrín
kíndìrín
temilade openiyi temilade ọpeniyi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1995 orúkọ tí àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ sí jùlọ ni tems ó jẹ́ akọrin ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà oǹkọ̀wé orin àti o ǹṣe àwo orin ìbẹ̀rẹ̀ ayé e rẹ̀ temilade ọpeniyi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1995 ní ipinle eko orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìyá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ...
dáníẹ́l o fágúnwà
pòtásíọ̀mù
ẹ̀ùkáríọ́tì
átọ̀mù
háídrójìn
abúlé abúlé jẹ́ ìlú kékeré tí àwọn ènìyàn ń gbé ó tóbi ju àbà lọ ṣùgbọ́n kò tóbi tó ìgboro bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé lọ́pọ̀ ìgbà ni àwọn ènìyàn máa ń pe àbà náà lábúlé òtítọ́ ibẹ̀ ni pé àbà kéré ju abúlé lọ abúlé sáàbà máa ń wà ní ìgbèríko tí wọ́n máa ń wà lábẹ́ ìgboro tí ó sìn ní ọ̀wọ́ àwọn olùgbé rẹ̀ àwọn ilé abúlé sáàbà máa...
àsìá ilẹ̀ karakalpakstan àsìá ilẹ̀ karakalpakstan je asia orile-ede
ògbàgì
keiko fujimori keiko fujimori jẹ iṣowo ti ilu peru ati oludari oselu ti o ṣiṣẹ bi first lady of perú lati 1994 si 2000 ati congresswoman fun metropolitan lima lati 2006 si 2011
adeniran ogunsanya adéníran ògúnsànyà qc san 31 january 1918 22 november 1996 jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú ibadan peoples party ipp ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún ìpínlẹ̀ èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́ẹ́kej...
adéníran ògúnsànyà college of education
yábàá college
ìlú ìkẹjà
mushin muṣin ni ó jẹ́ ìlú olókìkí ati agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ èkó musin ni ó wà ní apá 10 km àríwá ìpínlẹ̀ èkó àti gẹ̀rẹ́-gẹ̀rẹ́ àríwá ìpínlẹ̀ èkó ojú-ọ̀nà tí ó lọ sí ikeja muṣin sì wà lara àwọn agbègbè tí èrò pọ̀ sí jùlọ ní ìpínlẹ̀ èkó pẹ̀lú àwọn ilé olówó pọ́ọ́kú bákan náà ni ètò ìmọ́-tótó agbègbè náà kò ...
king's college lagos
àgbádárìgì
cooli carlito charlie omotunde ti a bi ni 30 oṣu kẹwa 1996 ti o mọ julọ nipasẹ orukọ ipele rẹ cooli carlito jẹ olorin ati oludasiṣẹ lati north west london igbesi aye ti ara ẹni a bi cooli carlito ni ilu lọndọnu england si iya gẹẹsi ati baba ọmọ naijiria kan iṣẹ cooli carlito bẹrẹ iṣẹ rẹ ni ọdun 2014 lakoko ti o nkawe n...
gẹẹsi