raw_text
stringlengths
2
128k
he sir patrick bijou
nigerian police nigerian government agency nigeria police jẹ́ ẹ̀ka pàtàkì nínú ilé-iṣẹ́ agbófinró ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí òfin àgbà orílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣe fi lélẹ̀ ní ọdún 1999 ilé-iṣẹ́ ọlọ́pá ní àṣẹ láti ní ẹ̀ka jákè-jádò orígun orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà tí yóò fi di ọdún 2016 àwọn tí wọ́n jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́...
ọlọ́pá orílẹ̀-èdè nàìjíríà
twitter twitter jé ìkànnì ibanidore lórí èro ayelujara o gbà àwon olùmúlò rè láti fi òrò ránsé si arawon àti láti fí òrò ranse sí afefe a lè lo ìkànnì ibadore twitter lórí èro alagbeka komputa tábìlì àti komputa alagbeka a da kalè ní odun 2006
mamarumo marokane south african actressmamarumo marokane bí ní 1997 jẹ́ òṣèré àti òlùṣètò south african wọ́n mọ̀ ọ́ fún ìfarahàn rẹ̀ ní shadow and mtv shuga ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí marokane ní ọdún 1996 láìmọ̀ àsìkò gan-an ó kàwé ní cityvarsity school of media and creative arts ó lè sọ èdè gẹ̀ẹ́sì èdè sepedi àti èdè se...
sthandiwe kgoroge sthandiwe kgoroge bí ní sithandiwe msomi ọjọ́ kẹ́rin oṣù kejì ọdún 1972 jẹ́ òṣèré south africa tó farahàn ní generations eré-ẹlẹ́lẹsẹ apá karùn-ún àti kejé ní mtv shuga eré-ẹlẹ́lẹsẹ kékeré mtv shuga alone together àti eré-ẹlẹ́lẹsẹ àkọ́kọ́ ti yizo yizo ìgbésí-ayé kgoroge gbé ní edmonton canada láti ọmọ...
nomalanga shozi jessica nomalanga shozi wọ́n bi ni ọdún1994 jẹ́ òṣèré south african díjè rẹ́dìó àti ènìyàn tó máa ń ṣe àfihàn lórí tẹlẹfísàn ó ṣe àfihàn lórí the soap rhythm city àti mtv shuga alone together bẹ́ẹ̀ náà ló ti jẹ́ olóòtú fún bet africa ayé rẹ̀ wọ́n bí shozi ni ọdún1994 àti wí pé ó dàgbà sókè ní port sheps...
kókó ọmú kókó omú tí àwon míràn mò sí orí omú jé ará omú tí o dide sita tí omi omú sì ún gbà jáde kókó omú àti agbegbe rèareola ma ún dúdú ju ara omú toku lo bí o tile jé wipe didusi kókó omú lè jé tori oyúnàwon oloye gbagbo pé ìdí èyi nipé kí omo ba le tete rí orí omú nígbà tí o ba fé jeun àkókò nkan osu tàbí tori aìs...
ọlọ́pàá orílẹ̀-èdè nàìjíríà
shuga naija shuga tí wọ́n pè ní shuga naija je eré-oníṣe-ẹlẹsẹsẹ tẹlẹfísọ̀nu kọ́kọ́ gba ìkéde lórí mtv base láti oṣù kejìlá ọdún 2013 títí di oṣù àkọ́kọ́ ọdún 2014 sáà náà jẹ́ kíkọ láti ọwọ́ kẹ́mi adésoyè àti jẹ́ ìdarí láti ọwọ́ bíyìí bándélé tí àwọn olórí òṣèré jẹ́ tíwá savage chris attoh maria okanrende emmanuel ikub...
sasha p nigerian singer and lawyer sasha p bí anthonia yetunde alabi ní ọjọ́ kọnkọ̀lélógún oṣù karùn-ún ọdún 1983 wọ́n tún mọ̀ ọ́ gẹ́gẹ́ bí ayaba híí-họpù nàìjíríà ó jẹ́ rápà nàìjíríà olórin obìnrin-onísọ̀wọ̀ agbẹjọ́rò àti olùwúnilórí ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó jẹ́ àbíkẹ̀yìn nínu ọmọ mẹ́jo ó jẹ́ ẹni tó jẹ́ w...
the department 2015 film by remi vaughn-richards the department jẹ́ fíìmù nàìjíríà ọdún 2015 tó dá lórí ròmáàsì ọ̀daràn ákísọ̀nù tí olùdarí rẹ̀ jẹ́ rẹ́mì vaughan-richards àwọn olórí òṣèré ni majid michel oc ukeje desmond elliot osas ighodaro jídé kosoko ṣeun akíndélé somkele iyamah funky mallam and kenneth okolie fíìmù...
the delivery boy the delivery boy tó fi ìṣòro ráńpẹ́ hàn tó jẹ́ kíkọ àti gba ìdarí láti ọwọ́ adékúnlé adéjùyígbé ó jẹ́ òǹṣe fíìmù àwọn gbajúmọ̀ fíìmù náà ni jẹ́ jammal ibrahim jẹ́mìnà osunde charles etubiebi kẹ́hìndé fáṣuyì àti àwọn olóòtú mìíràn delivery boy náà di wíwò ní film festivals pẹ̀lú african film festival ne...
shuha naija
ori orí gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara jẹ́ ẹ̀yà ara tí ó dúró lé ọrùn nínú orí ni a ti rí ojú imú ẹnu àti etí orí gẹ́gẹ́ bí ipò jẹ́ olùdarí leader ẹgbẹ́ kan tàbí ọ̀gbà kan orí sì tún lè túmọ̀ sí ìpín tàbí kádàrá ẹni orúkọ mìíràn fún orí tí ó dúró fún kádàrá ni àyànmọ́ tàbí orí inú ìwé ìtọ́kasí adekunle b o 2012 orí bíbọ láwùjọ yor...
us army school of infantry united states army infantry school tí ó wà ní ìlú fort benning ni ìpínlẹ̀ georgia jẹ́ ilé-ìwé tí ó wà fún kíkọ́ àwọn ológun ilẹ̀ amerika united states armed forces ètò ilé-ìwé llé-ìwé náà pín sí ẹ̀ka oríṣiríṣi bíi fún àwọn èèyàn to ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá àti...
command and staff college jaji senior military officer college armed forces command and staff college jaji jẹ́ ilé-ìgbẹ̀kọ́ fún àwọn nigerian armed forces pẹ̀lú àwọn ajagun orí òfurufú àti abẹ́-omi ó súnmọ́ ìlú jaji ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní apá àríwá ilẹ̀ kàdúná lábẹ́ ìjọba ìpínlẹ igabi lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí air vice mar...
special anti-robbery squad special anti-robbery squad tí òpòlopò ènìyàn mó sí sars jé aka olopa télè rí tí a dá kalè ní odun 1992 láti dojuko iwuwa odaran sùgbón tí opin dé bá ní ojó kokanla osù kewa odun 202011 oct 2020 léyìn iwode ifehonuhan láti owo awon odo nàìjíríà tí a mo sí iwode fopin sí sars iwode fopin sí sar...
david ibiyeomie ìránṣẹ́ ọlọ́run ní nàìjíríàa bi ni ọdún 1962 david ibiyeomie jé iranse olórun àti okowe ní orílè-èdè nàìjíríà oun ni olùdásílè àti adari ìjo salvation ministriestí o dá kalè ní odun 1997 tí olú ìjo wón wà ní ilu port-harcourt ìpínlè rivers nàìjirià a bi david ibiyeomie sí bonny island ìpínlè rivers ní k...
the green eyed green-eyed lady jẹ́ orin àdákọ tó gbajúmọ̀ láti ọwọ́ amẹ́ríkà rọọ̀kì baàdì sugarloaf ó di kíkọ lọ́wọ́jerry corbetta jc phillips àti david riordan wọ́n kọ́kọ́ fi orin yìí ṣe álíbọ̀mù wọn sugarloaf àti jẹ́ orin àdákọ wọn ó lọ sókè sí ipò kẹ́ta lórí billboard hot 100 ní ọdún 1970 àti wí pé ó jẹ́ orin àdákọ ...
femi adebayo femi adebayotí a bí ní ojó kokanlelogbon osù kejila odùn 1972 jé oserekunrin ní orílè-èdè nàìjirià abi sí ìlú eko adebayo salami tí òpòlopò eniyan mó sioga bello ni baba rè femi ka ìwé sekondiri ní ile-iwe cs college osi tèsíwájú ní yunifásitì ìlú ìlorin láti keko di amofin o kopa osere fún ìgbà akoko ninu...
àlá àlá jẹ orisirisi àwọn àwòrán àti àwọn àwọn èrò tí ó sábà máa ń ṣẹlẹ̀ láì si nkan to sokunfá nínú ọkàn nígba tí oorun ba de àwọn ìpele kan awọn eniyan nlo bi wakati meji ninu ala ni alẹ ati pe ala kọọkan gbá to iṣẹju marun si oogun itumo ati iṣẹ ti ala ni ti jẹ koko-ọrọ fun imọ ijinlẹ ati iwulo ẹsin jakejado itan ad...
awon omobìrin zelophehad àwon omobìrin zelophehad àwon omobìrin zelophehad tí a dárúko nínú bíbélì nínú ìwé númérì jé omo ìyá márun orúko won ni mahlah noa hoglah milcah ati tirzah wón jé òdómobìrin nígbà tí àwon omo israel n jáde kúrò ní ilè egypt tí wón sì n gbáradì lati wo ilè ìlérí wón gbéjó wá sí àkíyèsí àwùjo àwo...
idoti omi idoti omi jẹ ibajẹ ti omi nigbagbogbo onise pelu abajade awọn iṣẹ eniyan ni iru ọna ti o nipalara fun lilo re idoti omi maa dinku agbara ti omi ni lati pese awọn iṣẹ ailonka ti yoo pese bibẹẹkọ orisi apeere omi ni adagun awọn odo awọn okun omi kanga ati omi inu ile idoti omi maa njeyo latari dida idoti sinu a...
who's the boss ta ni ọ̀gá náà jẹ́ fíìmù olólùfẹ́-apanilẹ́rìn-ín ọdún 2020 nàìjíríà tó di ṣíṣejáde kíkọ àti darí láti ọwọ́ chinaza onuzo naz onuzo tó ma jẹ́ fíìmù àkọ́kọ́ tó má jẹ́ olùdarí fún eré náà fi sharon ooja fúnké akíndélé àti blossom chukwujekwu sẹ àwọn òṣèré tó kópa olórí fíìmù náà di wíwò fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ...
busiswa busiswa gqulu bí ní ọjọ́ kẹ́jọ oṣù kẹwàá ọdún 1988 wọ́n mọ orúkọ ọlọ́rọ̀ kan rẹ̀ sí busiswa tàbí busi jẹ́ olórin-akọrin àti akéwì south african wọ́n bi ní mthatha ìlà-oòrùn káàpù south africa ó di ìlú mọ̀ọ́ ká fún ìbáṣepọ̀ lórí orin dj zinhle orúkọ mi ni lẹ́yìn tó di mímọ lọ́dọ̀ kalawa jazmee's ọ̀gá ilé-iṣẹ́ os...
venita apkofure venita akpofure bíi ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 1987 big brother naija season 4ó jẹ́ òyìnbó-alawo dúdú british-nigerian tó sì jẹ́ òṣèré amóhùnmáworan ó jẹ́ gbajùmọ̀ ìlú mòoká lẹ́yìn tí ó jáde nínú ilé ẹ̀gbọ́n àgbà ìran ẹlẹ́ẹ̀kẹrin tí ayé mọ̀ sí big brother naija season 4 tí ó jé ara inú naa ò sí jẹ́ ak...
akojọ awọn olupilẹṣẹ fiimu naijiria èyí ni àkójọ àwọn tí wọ́n ṣe fílm̀ú ní orílé èdè nàìjíríà
list of nigerian film producers
aṣẹ ase tabi ashe lati yoruba àṣẹ jẹ́ yoruba philosophical concept nípa èyí tí yorùbá ti nàìjíríà lóyún agbára láti mú kí nǹkan ṣẹlẹ̀ àti láti mú ìyípadà wá o ti wa ni funni nipasẹ olodumare si ohun gbogbo — oriṣa ancestors ẹmí eda eniyan eranko eweko apata odo ati ohùn ọrọ gẹgẹbi awọn orin adura iyin egún tabi paapa l...
madagascar fílmu madagascar jẹ fílmu ti ere idaraya ará amẹ́ríkà
olori olori tí atún mò sí aya ọba tàbí iyawo oba jé iyawo sí oba tówà ní orí oyè ní àwon ìlú tàbí agbegbe tí asa wón gbà ki oba fé ju iyawo kan lo a le pe gbogbo ìyàwó oba ní ayaba bí o tile jé wípé ayaba jé eni iyi ní awujo ko ní agbara kankan lowo ararè ní òpòlopò àsà bi ní orílè-èdè united kingdomilẹ̀ọba aṣọ̀kan ati...
ayaba
kate henshaw kate henshaw tí a tún mọ̀ sí kate henshaw-nuttall wọ́n bi ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù keje ọdún 1971 jẹ́ gbajúmò eléré-orí ìtàgé ní ọdún 2008 ó gbégbá orókè ní african movie academy award fún ẹ̀dá ìtàn tí ó dára jù lọ nínú eré stronger than pain ibere aye kate henshaw jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ cross river òun sì ...
jhilmar lora jhilmar lora ojoibi 24 october 2000 ni callao lima je agbaboolu-elese to tifeyinti ara orile-ede perú
yemisi akinbobola yemisi akinbobola je onisowo iroyin omo naijria
sade adeniran sadé adéníran jẹ́ àràmàdà ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjírìa a bíi ńi ọdún 1960 àràmàdà ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ fojúinú wòyí gba àmì ẹ̀yẹ ònkọ̀wé àgbáyé ti ọdún 2008 fún ìwé àkọ́kọ́ tó dára jùlọ ní afíríkà fojúinú wòyí jẹ́ àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ nípasè ònkọ̀wé náà fún rara rẹ̀ ó ń gbé ní lo ndọ́nù ó tún jẹ́ òṣèré fíìmù
omolade akinremi omoladé akínrẹ̀mí jẹ ọmọ orílẹ́ èdè naìjírìa tí ó ti fẹ̀yìn tì nínú eré ìje hurdles ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kẹtàlá osù kẹsàń ọdún 1974
library ile ikawe je ibi akojopo orisirisi iwe amohun mo aworan ti o rorun lati lo ti kinsepe won wa fun pipate lasan eyi je ohun tin se akojopo ohun titun ti o ndahun ibeere ohun elo lojoojumo fun awon ayawe lo
rosaline bozemo rosaline bozemo jẹ́ agbẹjọ́rò àgbà ní ìpínlẹ̀ delta orílẹ̀ èdè nàíjírìa ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kìnní osù kìnní ọdún 1946
oliver mbamara oliver mbamara jẹ́ òsèré fíìmù olùkọ̀wé atẹwejáde ní naijiria ìwọ̀ òòrùn afirika
grace alele-williams grace alele-williams oon fman fnae tí a bí ní ọjọ kẹrìndínlógún ti oṣù kejìlá ọdún 1932 tí ó sì fi àyé sílè ní march 25 2022 jé òjògbón nínú ìmò mathi nígbà ayé rè grace alele-williams ní orúko ní ìtàn o jé obinrin àkókó tí o gbà àmì eye dokita ni nàìjíríà o sì jé obinrin àkókò tí ódi olori ilé-ìwé...
aishat abubakar aisha abubukartí a bí ní 20 july 1966 jé olósèlú ní orílè-ede nàìjirià ààre muhammadu buhari yàn gẹ́gẹ́ bí mínísítà fún ilé-iṣẹ́ okòwò ati investment ní ọdùn 2015 nì ọdùn 2018 ààre muhammadu buhari tún yàn àn gẹ́gẹ́ bí mínísítà fún òrò obínrin àti ìdàgbà-sókè àwùjọ olóṣèlú ni naijiria ìgbésí ayé àti ètò...
national institute for policy and strategic studies kuru national institute for policy and strategic studies nipss ní ìlú kuru ní orílẹ̀-èdè naijiria tí a dá sílẹ̀ ní ọdún 1979 jẹ́ àjọ tó ń rí sí ṣíṣe òfin fún àwọn olùdarí olórí àwọn ilé-iṣẹ́ àdáni àwọn olórí ogun àti àwọn òṣìṣẹ́ ìlú nípò kékeré àti ipò ńlá ọ̀pọ̀ àwọn ...
kuru kuru jẹ́ ìlú tó wà ní jos ní ipinle plateau ní apá gúúsù orílẹ́-èdè nàìjíríà ogún máìlì ló wà láàárí ìlú jos àti kuru àpapọ̀ ìlú kéréje abúlé àti agboolé tí ò jìnà síra ni ó wà ní kuru kuru pín sí méjì kuru a àti kuru b àpapọ̀ àwọn ìlú bíi danchol dakan dazek gwes hwak kushe vwei àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní ó bí kuru ìd...
iṣẹ́ fàyàwọ́ iṣẹ́ fàyàwọ́ ni gbígbé ẹrù ohun èlò tàbí èèyàn lọ́nà àìtọ́ láti ibikan sí ibòmìíràn ó le jẹ́ láti ìlú kan sí ìlú mìíràn tàbí láti orílẹ̀-èdè kan sí orílẹ̀-èdè mìíràn
human trafficking in nigeria kíkó àwọn ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́ láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ ìrìn àjò tó ní ṣe pẹ̀lú gbígbé obìnrin ọmọdé àti ọkùnrin lọ́nà àìtọ́ láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà sí òmíràn látàri pípa iró tàbí títan àwọn ènìyàn tó ń wá ìgbésí ayé ìrọ̀rùn jẹ ìtàn ní ọdún 2001 àjo naptip ṣe àfilólè wí pé w...
ìrìn àjò ọ̀nà ẹ̀bùrú ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
kíkó àwọn ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
ajo national agency for the prohibition of trafficking in persons national agency for the prohibition of trafficking in persons naptip jẹ́ àjọ agbófinró ìjọba-àpapọ̀ orílè-èdè nàìjíríà tí wọ́n dá sílẹ̀ lọ́dún 2003 láti gbógun ti kíkó ènìyàn lọ sí òkè-òkun lọ́nà àìtó àti àwọn ọ̀ràn mìíràn tó jẹ́ mọ àtakò ẹ̀tọ́ ọmọ-ènìyà...
action against trafficking in persons and smuggling of migrants in nigeria a-tipsom action against trafficking in persons and smuggling of migrants in nigeria tí ó bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2018 látàri àjọmọ̀ tó wà láàárín àjọ european union àti ìjọba orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ àjọ tó ń rí sí ìdínkù gbígbé àwọn èèyàn láti oríẹ-ede n...
ìfọmọdé ṣiṣẹ́ ipá child labour in nigeria ìfọmọdé ṣiṣẹ́ ipá ni a lè pè ní ọ̀nà ìlo ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ láti lè jè kí àwọn ọmọdé ó má ní ànfaní sí ẹ̀tọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ọmọdé tàbí ète láti lè jẹ́ kí wọ́n má ní ànfaní sí ẹ̀kọ́ nígbà èwe èyí jẹ́ ohun búburú tí ó ń gbégidínà ẹ̀tọ́ àwọn ògo wẹẹrẹ àwọn ìṣesí sí àwọn ọmọdé wọ̀nyí ni w...
child harvesting in nigeria child harvesting in nigeria o tumo si pe ona ti awon eniyan gba bi omo ni ona ti ko bojumu ati bi awon alagbato ni awon ilu nla se n gba omo to fun idi kan tabi omiraneyi tumo si fifi omo se pasiparo lori eto igbokegbodo oro aje ni tipatipa ati agidiopolopo awon omodebinrin ti ojo ori won ko...
network of csos against trafficking abuse and labour nactal nigerian umbrella network against human traffickingnetwork of csos against trafficking abuse and labour jẹ́ àjọ tó ní àfojúsùn àti dáàbò bo ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn àti láti mú àwọn olùfaragbá tí wọ́n ti gbé lọ sí ìlú mìíràn lọ́nà àìtọ́ tí ó sì ti jìyà látàri ṣíṣe iṣẹ...
kíkó àwọn ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́ láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà
2015 trafficking in person prohibition and enforcement act 2015 trafficking in person prohibition and enforcement act jẹ́ àbádòfin ti wọ́n ṣe lọ́dún 2015 láti dẹ́kun ọ̀ràn kíkó ọmọ ènìyàn ròkè òkun lọ́nà àìtọ́ pẹ̀lú èròǹgbà láti rẹ́ wọn jẹ́ nínú òógùn-iṣẹ́ wọn ìpìlẹ̀ṣẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ kò sí òfin kan gbòógì tí wọ́n f...
child trafficking in nigeria child trafficking in nigeria jẹ́ kíkó ọmọdé lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́ o sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tó pọ̀ ní ilẹ̀ òkèèrè àti ilẹ̀ adúláwọ̀ kódà a ò lè sọ wí pé ìlú kan lára rẹ̀ mọ́ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ àmọ́ bí ẹ̀ṣẹ̀ yìí ṣe pọ̀ tó ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni ò nímọ̀ tó yanjú nípa rẹ̀ kí a sọ ojú ...
ministry of humanitarian affairs disaster management and social development àjọ ministry of humanitarian affairs disaster management and social development jẹ́ àjọ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà kan tí ó ń mójútó ìgbáyé-gbádùn íbójútó ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì àti ígbélárugẹ ní àwùjọ ọmọnìyàn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n dá àj...
west african coalition against trafficking in person and smuggling of migrant in nigeria wactipsom west african coalition against trafficking in person and smuggling of migrant in nigeria wactipsom jẹ́ ìsọ̀kan àwọn orílẹ̀ èdè adúláwọ̀ láti gbógun ti gbígbé tàbí kíkó àwọn ènìyàn káàkiri ní ọ̀nà àìtọ́ àti rírin ìrìn àjò ...
network of csos against trafficking abuse and labour
pope alexander i
pope leo xi
pope agapetus i
pope urban v
pope john xii
pope celestine iii
pope john iii
pope honorius i
pope sergius i
pope gelasius i
pope adeodatus ii
pope benedict i
pope pelagius ii
pope sixtus i
pope sergius ii
pope leo viii
pope benedict v
pope paschal ii
pope john xiii
pope paul ii
pope john xxii
pope gregory ix
pope gregory iii
pope clement v
pope nicholas i
pope martin iv
pope gregory x
pope eugene iv
pope theodore i
pope gregory vii
pope benedict vi
pope benedict vii
pope urban viii
pope innocent xiii
pope alexander vii
pope sixtus v
pope clement vii
pope clement xii
pope benedict xiii
pope john vi