raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
michael aondoaka michael aondoaka jẹ́ agbẹjọ́ro àgbà ilẹ̀ nàìjíríà láti ọdún 2007 títí di 2010 ó jẹ́ ọmọ bíbí ilé benue tí àbí ni ọdún 1962 ẹgbẹ legal practitioners privileges committee ti orílẹ-èdè nàìjíría gba ipò senior advocate of nigeria san lówó aondoakaa ni 2010 |
mir koks/draft |
chico ejiro chico ejiro tí a bí ní chico maziakpono kú lójó 25 oṣù kejìlá ọdún 2020 jẹ́ oludarí fíìmù nàìjíríà ònkọ̀wé eré ìtàgé àti olupìlẹṣẹ̀ ejiro jẹ́ ọmọ isoko delta nàìjíría tí ó kọ èkọ́ iṣẹ-ogbin ní ilé ìwé èkó gíga ara iṣẹ́ nlá rẹ̀ jẹ́ aṣojú ti iran keji ti o bẹ̀rẹ̀ ní àwọn ọdún 1990 nígbàtí ohun èlò ìṣelọ́pọ̀ f... |
cheikh ndiaye cheikh ndiaye je òṣèré àti ònkọ̀wé láti ìpínlè senegal ó ka editing and filmmaking ní free conservatory of french cinema clcf ní ìpínlè fránsìó ṣe àgbéjáde ìwé ìtàn mẹ́rin pẹ̀lú sira badral ati àwọn fíìmù ìtàn-àkọ́ọ́lé méjì |
àpá lagos apá jẹ́ ọ̀kan lara àwọn ìlu tí ọjọ rẹ̀ pẹjulọ labẹ ijọba ibilẹ agbadrigi no ijọba ipinlẹ ekoaṣeeṣe ọmọ odudua lati ile ifẹ̀ tojẹ awori lotẹ ilu yi do ni ọrundun kejila 1200 ad ni ila oorun o paala pẹluu agbadarigini iwọ oorun o paala pẹlu inọgini guusu opaala pẹluu okun ni ẹnubode sẹmẹni ariwa o paala pẹluu ọ... |
devil in agbada bìlísì nínú agbada jẹ́ eré 2021 ti orílẹ̀-èdè nàìjíríàchinneylove eze lo ko fíìmù náà ati umanu elijah lo 'ludari rẹ̀ awọn oṣere fíìmù náà ni erica nlewedim linda osifo àti efe irele awọran ti fíìmù náà jáde ni march 2021 fíìmù naa ni iṣafihan pàtàkì rẹ ni oṣu karun ọjọ ketadinlogbon odun 2021 àti pe o ... |
descent 2017 film descent jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí bridget phathudi kọ abdulfatai awal tí nwankwo chibuzor ṣe àti oludari rẹ̀ ni abdulfatai awal fíìmù naa ṣe afihan ni sinima ni oṣu kejila ọjọ kini ọdun 2017 fíìmù naa n se ṣapejuwe àwọn ọran tí o jọmọ idile ogun oloro ifẹ ẹ̀san àti ọpọlọpọ nkan die sii descent ... |
ebonylife tv ebonylife tv jé tẹlifisiọnu ìkànnì fun ìdánilárayáohun ìní nipasẹ mosúnmólá abudu gbàjúmò ti a npe ni mo abuduo ti ṣe ìfilọlẹ lóri dstv ni oṣù keje ọdún 2013 lẹhìn èyí a ti fi ìbùdó naa kún si dstv ni oṣù kẹsan 2014lẹhìn àjọṣepọ àti ìtẹlọrùn iṣeto aláse ebonylife tv ni pẹlú dstv fun ju ọdún márun |
ruth ndulu maingi ruth ndulu maingi tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kàrún ọdún 1983 jẹ́ òṣèré orílẹ̀ ède kenya kan ó jẹ́ olókìkí fún àwọn ipa tí ó ti kó nínú àwọn eré oníse 18 the distant boat and midlife crisis ìgbésí ayé rẹ̀ a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kàrún ọdún 1983 ní ìlú machakos orílẹ̀ ède kenya tí ó sì jẹ́ ẹ̀ẹ... |
constantine kanaris |
ìséyìn |
ayẹyẹ fíìmù gbogbo obìrin káríayé ni salé ayẹyẹ fíìmù awọn obirin káríayé ti salé larubawa المهرجان الدولي لفيلم المرأة بسلا tabi fiffs jẹ ajọdun fiimu ti o waye ni salé morocco ti a ṣeto nipasẹ ẹgbẹ bouregreg labẹ ìṣàkóso ti ọba mohammed vi pẹlu ero lati ṣe igbega si sinima obinrin ati fifi awọn obinrin han ni sinima ... |
mbeki mwalimu mbeki mwalimu jẹ́ òṣèré ará kenya olùdásílẹ̀ àti olùdarí tí ó ju ọdún mẹ̀wá lọ nínú eré ìtàgé àti ìrírí tv ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní ibi ìṣeré ti kenya ní ọdún 2004 ní mbalamwezi players ṣaájú kí ó darapọ̀ mọ́ festival of creative arts fca ní ọdún 2007 àti pé láti ìgbà náà ó ti di orúkọ tí a mọ̀ mó ọ gẹ́gẹ́ bí... |
ẹ̀sìn hinduism hinduism jẹ ẹsin india eyiti o jẹ ẹsin kẹta ti o tobi julọ lẹhin kristiẹniti ati islam |
ọyẹ́ ọyẹ́ jẹ́ àsìkò kan lápá ìwọ̀-oòrùn áfíríkà tí ó má a ń wáyé láàárín ìparí oṣù kọkànlá sí àárín oṣù kẹta ọdún ó jẹ́ àsìkò ẹrùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀ tí ó máa ń fa eruku orúkọ náà farajọ ọ̀rọ̀ náà ọyẹ́ ní èdè twi ó má a ń jẹ́ àsìkò òtútù ní àwọn àgbègbè mìíràn ẹ̀wẹ̀ ó máa ń jẹ́ àsìkò oru èyí máa ń dá lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọ... |
teni olórin teniola apata tí a bí ní 23 oṣù kejìlá ọdún 1992 tí a mọ̀ sí teni jẹ́ akọrin ati amúlúdún ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbésí ayé àti ìbẹ̀rẹ̀ orin rẹ̀ a bí teni ní 23 oṣù kejìlá ọdún 1992 ni ìpínlẹ̀ èkó ó jẹ́ àbúrò olórin ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí à ń pè ní niniola ó kàwé ni lé ìwé gírámà apata memorial high sc... |
ìṣègùn ìbílẹ̀ is̩é̩ ìs̩ègùn jé̩ ò̩kan gbòógì nínú is̩é̩ ìs̩è̩ǹbáyé yorùbá ààbò è̩mí àti dúkìá pè̩lú wíwa ojútùú sí onírúurú ìs̩òro è̩dá ni kókó tí is̩é̩ ìs̩ègùn dálé ewé egbò àti gbogbo è̩dá yàlá abè̩mí tí ó wà ní orí ilè̩ àti inú omi ni wó̩n ń lò fún is̩é̩ ìs̩ègùn àjò̩ ètò ìlera àgbáyé world health organization sọ pé ... |
àkànlò èdè áyàwòrán e̩wà èdè ni àkànlò èdè jé̩ nis̩e ni àkànlò èdè máa ń ya àwòran sí o̩kàn e̩ni tí ó bá gbo̩ sétí tàbí tí ó bá kà á nínú ìwé ìtumò̩ méjì ni àkànlò èdè máa ń ní ìtumò̩ eréfèé àti ìtumò̩ ìjìnlè ajíbóyè 200257 s̩e àpèjúwe àkànlò èdè ayàwòrán gé̩gé̩ bíi àwo̩n hóró ò̩rò̩ àpólà tàbí gbólóhùn tí as̩afò̩ lò lá... |
ilojo bar ilojo bar tí wọ́n tún ń pè ní ilé ọláìyá tàbí casa da fernández jẹ́ ilé ìṣẹ̀ǹbáyé tí wọ́n kọ́ bí ti àwọn brazil tí ó wà ní tinubu square lagos island ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà orúkọ ilojo bar lẹ́yìn tí wọ́n tá ilé náà fún alfred omolona ní ọdún 1933 o yí orúkọ rẹ dà sí “ilojo èyí tí ó jẹ́ orúkọ ìlú r... |
historic quarter of the city of colonia del sacramento ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ sacramento california colonia del sacramento jẹ ilu ni apa guusu iwọ-oorun uruguay ni ẹgbẹ río de la plata ti ọ kọjú si buenos aires argentina o jẹ ọkan ninu awọn ilu atijọ julọ ni uruguay ati olu-ilu nígbà aye ijọba amunisin awon ti o wa ni... |
lamu old town lamu tàbí ìlú lamu jẹ́ ìlú kékeré ni erékùṣù lamu tí o jẹ́ apá kan lára lamu archipelago ni kenya ó wà ní ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà 341 212 mi ní ojú ọ̀nà ilá-oòrùn àríwá tí mombasa ó sì parí sí èbúté mokowe níbi tí a níláti gba ọ̀sà kọjá lọ sí erékùṣù lamu òun ni olú iléeṣẹ́ àgbègbè lamu àti ibùdó ohun àjogúnbá àg... |
historic centre of arequipa ni osu kejila odun 2000 unesco kede ibi historical center of arequipa gẹgẹ bi world heritage site nipa sisọ awọn ohun wọnyi ibi historical center of arequipa jẹ apẹrẹ ornamented architecture osi duro gẹgẹbi iṣẹ asetan ti ojade lati iparapọ awọn iwa ti oyinbo ati awọn abinibiilu amunisin ti o... |
historic inner city of paramaribo capital of surinameparamaribo nicknamed par'bo jẹ olu-ilu ati ilu ti o tobi julọ ti suriname ti o wa ni awọn bèbe ti odò suriname ni agbegbe paramaribo paramaribo ni iye eniyan ti o to 241000 eniyan ikaniyan 2012 o fẹrẹ to idaji awọn olugbe suriname ilu inu itan ti paramaribo ti jẹ iko... |
historic centre of lima world heritage site in peru ti a da ni akọkọ so aarin ilu tabi cercado dé lima ati agbegbe rimac historic centre of lima wa lára àwọn ibi ti o sé pataki julọ ti awọn arinrin-ọjọ ma nifẹ lati de located principally in the city centre or cercado de lima and rímac areas the historic centre of lima ... |
खाबी लंगडा redirect due to inappropriate source |
ghánà |
cusco ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the city fún ìtumọ́ míràn ẹ wo cusco ìṣojútùúcusco ti wọn má shi kọ nigba miran si cuzco jẹ ilu kan ni guusu ila-oorun perú nitosi afonifoji urubamba ti awọn oke andes o jẹ olu-ilu ti ẹkun cusco ati ti agbegbe cusco ilu naa jẹ inu keje ti o pọ julọ nipa olugbe ni perú ati ni ọdun 2017 ni iy... |
cidade velha cidade velha portuguese city atijọ́ tabí santiago de cabo verde jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní apá ìlà oòrùn erékùṣù santiago cape verde wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 146277 òun ni ó jẹ́ ìlú tí ó pẹ́ jùlọ ní agbégbè cape verde tí ojẹ́ olú ìlú ibé tẹ́lẹ̀ wọ́n ti fìgbà kan rí pèé ní ribeira grande wọ́n sì yi padà sícidade v... |
erékùṣù mozambique erékùṣù mozambique ni o wà ní ẹ̀yìn àríwá ilẹ̀ mozambique láàrín mozambique channel àti ẹsẹ̀ odò mossuril ó sì wà ní ara nampula province ṣáájú ọdún 1898 òun ni olú-ìlú fún portuguese east africa ní àsìkò ìmúnisìn erékùṣù mozambique ni ó wà lára àwọn unesco world heritage site látàrí àwọn ohun ọ̀ṣọ́ ... |
abba abba jẹ́ ẹgbẹ́ were an sweden olórin pop ará swídìn tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìlú stockholm ní 1972 pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó ní akọrin agnetha fältskog anni-frid lyngstad björn ulvaeus àti benny andersson |
grand bassam grand-bassam jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní apá ìlà-oòrùn orílẹ̀-èdè ivory coast tí ko fi bẹ́ẹ̀ jìnà sí ìlú abidjan ìlú yí jẹ́ ikan lára àwọn tí grand-bassam ti ń ṣe ìjọba ó sì tún jẹ́ ibùgbé fún àwọn ara ivory coast lásìkò ọ̀rùndún kẹrìnlélógún grand bassam ni ó jẹ́ ola ìlú ati ibi tí ilé iṣẹ́ ìjọba àwọn faransé ... |
selena gomez selena gomez ti a bi 9 oṣu kẹta ọdun 1992 jẹ singer ti o jẹ ọmọ ilu usa ti o da ni california igbesi aye ibẹrẹ ati iṣẹ a bi lame ni texas ni ọjọ 9 oṣu kẹta ọdun 1992 awọn ẹbi rẹ gbe lọ si ile -iṣẹ ti gbogbo eniyan ni california nigbati o jẹ ọmọ ọdun kan o ni meta tegbotaburo gomez ṣiṣẹ gẹgẹbi oniṣẹ ẹrọ cnc... |
billie eilish billie eilish 2001 |
agnetha fältskog agnetha fältskog oruko abiso agneta åse fältskog jönköping sweden 5 april 1950 je olorin ara sweden to gbajumo daada gegebi asiwaju akorin ati akoweorin egbe olorin pop abba |
anni-frid lyngstad anni-frid „frida“ synni lyngstad narnik norway 15 november 1945 je ara sweden akori asaju ati amorindun egbe olorin pop abba |
old town of ghadames unesco world heritage site in ghadames libya old town of ghadames lárúbáwá ni ó jẹ́ ìlú atìjọ́ kan tí wọ́n ń pè ní ghadames tí ó wà ní orílẹ̀-èdè libya tí ó sì jẹ́ ìkan nínú ìlú tí ó wà ní ilẹ̀ aṣálẹ̀ ní orílẹ̀-èdè libya tí wọ́n ń pè ní jewel of the desert wọ́n fi ìlú náà sí abẹ́ unesco world her... |
medina of essaouira medina of essaouira tí a mọ̀ sí mogador tẹ́lẹ̀ ni ó jẹ́ ìdá kan nínú ìdá mẹ́rin ìlú medina tí ó wà ní essaouira ní orílẹ̀-èdè morocco àjọ unesco sọ ibẹ̀ si ibi àbojúwò world heritage site ní ọdún 2001 ìtàn essaouira ni ó jẹ́ àpẹẹrẹ ìlú tí ó yàtọ̀ gidi láti òrùndún kejìdínlógún tí wọ́n kọ́ pẹ̀lú ìlan... |
medina of tetouan medina of tetouan ni ó wà ní ara àwọn ìpín mẹ́rin ilẹ̀ medina ní tetouan ní orílẹ̀-èdè morocco àjọ unesco sọ ibẹ̀ di world heritage site ní ọdún 1985 ìtàn tétouan ni ó jẹ́ ìkan nínú àwọn ìlú tó lààmì-laaka ní àsìkò ìpolongo ẹ̀sìn mùsùlùmí ìyẹn láti ọ̀rùndún kẹjọ sìwájù si ìlú yí jẹ́ ìlú tí ó so morocc... |
medina of sousse medina of sousse ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpín mẹ́rin ilẹ̀ medina ní sousse governorate of sousse ní orílẹ̀-èdè tunisia àjọ unesco sọ ibẹ̀ di world heritage site ní ọdún 1988 ìlú yí fi àpẹẹrẹ ìṣèjọba ẹ̀sìn mùsùlùmí hàn pẹ̀lú àwọn ilé aláràmbara tí wọ́n ti kọ́ ní aìmọye ọdún ẹ́yìn ní agbègbè maghreb lár... |
ichan kala world heritage site in khiva uzbekistan ichan kala ìlú tí wọ́n mọdi yíká tí ó wà ní khival ní ùsbẹ̀kìstán ìlú yí ti wà lábẹ́ ìnojúwò ati ìdáàbòbò àjọ world heritage site láti ọdún 1990 ìlú àtijọ́ yí ní àwọn ibi ìtàn ní agbáyé tí ó tó àádọ́ta tí wọ́n sì ti wà láti ọ̀rùndún kejìdínlógún tabí kọkàndínlógún sẹ́y... |
old town of prague old town of prague tsẹ́kì nibó jẹ́ ìletò kan tí ó ti wà tipẹ́ ní ìlú prague ní orílẹ̀-èdè czech republic wọ́n yà á sọ́tọ̀ láti ìta pẹ̀lú odi kérébété kan tí wọ́n pè ní vltava tí ó sì ní odò ní apá ọ̀tún ati apá òsì kòtò yí ni wọ́n fi òpópó oríṣiríṣi bò mọ́lẹ̀ láti apá north sí south-west revoluční na... |
tallinn old town tallinn old town is the oldest part of tallinn estonia old town of tallinn has managed to wholly preserve its structure of medieval and hanseatic origin old town represents an exceptionally intact 13th century city plan since 1997 the area has been registered in the unesco world heritage list the old t... |
old towns of djenné ìlú old towns of djenné jẹ́ ílú tí èrò pọ̀ sí gidi tí ó wà ní djenné ní orílẹ̀-èdè mali àwọn ibi mẹ́rin kan wà nílú yí tí wọ́ n ń gbé ìlú yí níyì àwọn ni djenné-djeno hambarkétolo kaniana àti tonomba ọdún 1988 ni àjọ unesco fi ìlú yí sí abẹ́ ìbojúwò wọn ni world heritage list ìtàn àwọn ará djenné ti... |
jewish quarter and st procopius' basilica in třebíč jewish quarter and st procopius' basilica in třebíč ni ó jẹ́ orúkọ tí wọ́n fi sílẹ̀ sí abẹ́ iṣẹ́ àkànṣe àjọ unesco world heritage site in třebíč czech republic àwọn ìletò tó wà níbẹ̀ ni |
èdè interlingue interlingue ni occidental ti o ti kọja jẹ ede oluranlọwọ kariaye ti o ṣẹda nipasẹ edgar de wahl ati ti a tẹjade ni ọdun 1922 litireso awọn ọrọ iwe-kikọ akọkọ ni interlingue han ni cosmoglotta àwọn iṣẹ́ kan tún wà àwọn tí wọ́n jẹ́ ìpilẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn tí wọ́n túmọ̀ tí wọ́n tẹ̀ jáde ní interlingue awọn ọrọ ... |
awọn eniyan roma awọn ara ilu romania jẹ ẹya indo-aryan awọn arinrin ajo ti aṣa ti o ngbe pupọ julọ ni yuroopu ati awọn olugbe ilu okeere ni amẹrika romani gẹgẹbi eniyan ti wa lati iha ariwa india lati rajasthan haryana ati awọn agbegbe punjab ti india ode oni yi ni a kukuru article jọwọ mu yi |
rinsa malone rinsa malone jẹ akọrin ati grime mc lati north west london a bi ni paddington o si dagba ni camden o si lọ gbogun ti fun orin rẹ “ṣi oju oju kan” eyiti o jade ni ọjọ 6 oṣu kini ọdun 2022 |
tampere tampere sv tammerfors jẹ ilu inu ilẹ ni fínlándì o wa ni ibuso 180 ni ariwa ti helsinki olu-ilu naa o fẹrẹ to eniyan 250000 ngbe ni tampere |
suya suya tàbí skewer tí àṣà tí àṣà mú skewer tí o wà láti ariwa naijiria ilẹ̀ hausa àti pé o jẹ́ oúnjẹ tí o gbajúmọ̀ ni iwọ-oorun afirika suya tún n pé ní soya jẹ́ ẹyà nla ninu àṣà àti oúnjẹ hausa àti itan-akọọlẹ tí pèsè ati ṣe nipasẹ àwọn ọkùnrin hausa 'mai nama' kìí ṣẹ àwọn obìnrin suya ní gbogbogbò ní a ṣẹ pẹlú ẹra... |
gàrí gàrí ni ohun jíjẹ lẹ́bú-lẹ́bú kan tí ó ma ń ní awọ funfun tabí àwọ̀ órí tí wọ́n ma ń ṣe jáde láti ara ẹ̀gẹ́ tí a tún ń pè ní pákí irúfẹ́ ounjẹ yí wọ́pọ̀ ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ adúláwọ̀ oríṣiríṣi ohun tí wọ́n pèsè láti ara nkan bíi àgbàdo ìrẹsì iṣu tàbí ọkà bàbà tí wọ́n sì sọ di ìyẹ̀fun ni àwọn ẹ̀yà hausa sábà ma ń... |
ẹ̀bà ẹ̀bà jẹ́ óuńjẹ òkèlè tí wọ́n ma ń jẹ ní apá ilẹ̀ adúláwọ̀ ati agbègbè rẹ̀ pàá pàá jùlọ ní orílé-èdè nàìjíríà àti gánà ẹ̀bà ni àwọn ẹ̀yà yorùbá sábà ń pèé ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà it is a cooked starchy vegetable food made from dried grated cassava manioc flour commonly known as gàrí bí a ṣe ń tẹ ẹ̀bà a ó gbé omi ka ... |
linda ikeji linda ifeoma ikeji tí a bí ní ọjọ́ kọkándínlógún oṣù kẹsàn án ọdún 1980 jẹ́ òǹkọ̀wé oníṣòwò òǹkòwé sínú ìwé ìròyìn ti orí ẹ̀ro-ayélujára àti ẹni tí ó ti jẹ́ aláwòṣe ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà linda jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nítorí ìwé tí ó ma ńkọ sínú ìwé ìròyìn lórí ẹ̀rọ-ayélujára àti wípé àwọn ìwé kíkọ rẹ̀ yí sábà ma ... |
teni singer |
jalingo city stadium the jolly nyame stadium jẹ́ pápá ìdárayá tí wọ́n lè lò fún oun kóun ní jalingo nàìjíríà wọn máa ń sábà lòó fún bọ́ọ̀lù gbígba ó sì jẹ́ pápá ìdárayá fún taraba fc wọn kọ́ pápá ìdárayá yìí ní ọdún 2002 o sì lè gba èèyàn bíi 30000 |
afirika amẹrika awọn ọmọ afirika amẹrika ti a tọka si bi black america ati tẹlẹ afro-amẹrika jẹ ẹgbẹ ẹya ti o ni awọn ara amẹrika ti o ni apakan tabi idile lapapọ lati eyikeyi awọn ẹgbẹ alawọ dudu ti afirika yi ni a kukuru article jọwọ mu yi |
ajibade gbadegesin ogunoye ajibade gbadegesin ogunoye je agbejoro osise ipinle ondo tele o si je oba ilu owo ise re o je oba leyin ti oba ana folagbade olateru olagbegi iii papo'da kí ó tó di ọba ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìjọba ìpínlẹ̀ òndó gẹ́gẹ́ bí adarí ìṣàkóso ìṣúná lábẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ ondo awon itokasi ' |
àrùn ọkàn àrùn okàn jé ọrò gbogbògbò tí a lò láti ṣe àpèjuwe èyíkéyi nínú àrùn tí o kan ọkàn àti/tàbí àwọn ohun èlò èjè wọn pẹlu orisirisi iru àrùn bi ìkùnà okàn àti aìsàn okàn míràn àrùn ọkàn jé okunfa ikú fun awọn ọkunrin awọn obinrin ati eniyan awọn òpòlopò èyà ni ilu amẹrika |
okemesi ilu okemesi-ekiti je ijoba ibile kan ni ipinle ekiti ti o wa ni guusu-iwoorun naijiria olugbe rẹ gẹgẹbi ikaniyan olugbe odun 2006 jẹ awọn olugbe egberun lona ogofa odin merin 56000 agbègbè okemesi-ekiti wa ni guusu-iwọ-oorun ti nigeria ti o wa laarin ilẹ-ilẹ ti olooru ni agbegbe igbo ojo o wa lori latitude 782°... |
adekunle akinlade adekunle akinlade a bi adekunle abdulkabir akinlade ni ojo kesan osu kewa odun 1969 je oloselu omo orile ede naijiria o je asoju guusu egbado ati poa ni ile igbimo asofin agba ti orile ede naijiria o dije ipo gomina je gomina ipinle ogun |
hospital-acquired infection akoran ti a ko lati ile iwosan ti a tun mo si akoran nosokomia jẹ akoran ti a ko lati ile iwosan tabi ibi ti a ti n wo awon alaisan lati le je ki awon eniyan mo iyato laarin awon akoran ti a ko ni ile iwosan ati eyi ti a o ko ni ile iwosan a maa n pe ni akoran ile itojuakoran ti ile itoju il... |
akoran ti a ko lati ile iwosan àkóràn tí a kó láti ilé ìwòsàn tí a tún mò sí àkóràn nosocmial jẹ́ àkóràn tí a kó láti ilé ìwòsàn tàbí ibi ti a ti ń wo àwọn aláìsàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà ni ènìyàn ti le kọ́ ààrùn ní ilé ìwòsàn ó lè jẹ́ nípa àìkíyèsí ara nígbà tí ènìyàn bá ń lo àwọn nkan èlò ilé ìwòsàn tí ààrùn ti wà lára rẹ̀ ... |
egboogi lumefantrine lumefantrine tabi benflumetol jẹ oogun egboogi-ibà lilo re gbodo je pelu artemether nikan nigba mii a maa n se apejuwe re gege bii akole apapo artemether lumenfantrine maa n duro pe ninu ara ju artemether lo ati pe eyi je ki a ro wipe o maa n se akotan kokoro aifojuri afaisan ti o ba seku sinu ago ... |
lumefantrine |
keke maruwa keke márúwá tàbí kẹkẹ napep je katakata ẹlẹsẹ mẹta ti afi nṣe kabúkabú ni orile-ede nàìjíríà wọn bẹrẹ lílò kẹkẹ yi ní ìgbà ti ọ̀gágun mohammed buba marwa jẹ gómìnà ìpínlẹ̀ èkó ní abẹ́ ìṣàkóso ológun o kéré ni ìwọnba osi gba ènìyàn mẹta lẹyìn pẹlú awakọ kan soso ni iwájú |
ezenwo nyesom wike |
sepeteri nàìjíríà |
kishi |
james peace a bí kẹ́néẹ̀ti jèmíìsì píìsì ní páísílì èdè gẹ̀ẹ́sì paisley ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1963 ọmọ ilẹ̀ skọ́tlándì tí ó máa ń kọ orin sílẹ̀ tí ó máa ń tẹ pianó níbi tí wọ́n bá ti ń kọrin ní ìta gban̄gba tí ó sì máa ń ya àwòrán ni ìgbé ayé rẹ̀ a bí jèmíìsì píìsì ní páísílí ní ilẹ̀ skọ́tlándì ní ... |
mayorkun nigerian musician adewale mayowa emmanuel wọ́n bi ní 23 oṣù kẹta ọdún1994 wọ́n mọ̀ ọ́ sí mayorkun tí í ṣe orúkọ iṣẹ́ àti orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ó jẹ́ olórin àti akọrin tí ó máa ń kọ orin tí ó wá láti orílẹ́-èdè nàìjíríà ó kọ orin àṣehàn fún orin davido' kan tí í ṣe the moneyní orí ẹ̀rọ twitter níbi tí davido ti rí ... |
oba saheed ademola elegushi kabiesi oba alayeluwa saheed ademola elegushi kusenla iii ara oba ileyoruba ni naijiria won bi ni 10 osu kerin 1976 ohun ni okan le logun elegushi ti ile ilu ikate-elegushi oba elegushi je omo oba idile kusenla ti ilu ikate ni ipinle eko o gbade leyin ipakoda baba e iyen oba yekini adeniyi e... |
seun osewa oluwaseun temitope osewa december 17 1982 jẹ oluṣowo intanẹẹti kan ti orilẹ-ede naijiria oun ni oludasile nairaland apejọ intanẹẹti ti o gbajumọ ti a ṣe ifilọlẹ ni oṣu kẹta ọdun 2005 forbes sọ pe nairaland jẹ apejọ ti o tobi julọ ni afirika iṣẹ seun bẹrẹ nairaland ni ọdun 2005 |
oluwaseun osowobi oluwaseun ayodeji osowobi je ajafeto omo obirin ni naijiria ohun ni oludasile ati alakoso stand to end rape ster initiative ni odun 2019 ohun ni obirin naijiria elekeji ti won fi ami idanimo akojo time 100 next dalola be si ti nu pe otun gba ami eye ti commonwealth young person of the year fun odun 20... |
àrùn ọpọlọ àrùn ọpọlọtí a ma ùn pe ni stroki jẹ ipo ibajẹ si ọpọlọ to o ma ún selè nitori idilọwọ ipese ẹjẹ o le jé idinku gidigidi si èjè tó lo si opolo tabi idaduro patapata àrùn opolo ma ún yori si ailera awọn iṣan tabi ìropá rosè ni ẹgbẹ kan araole jé apá òtún tàbí ti osi ó jé àrùn asiwaju keta to un fa ikú ni àgbá... |
isanraju ìsanra púpọ̀ jẹ́ ipò ti òrá wà nínú ara tí ó sì lè mú ewu bá ara a ma sọ pe ènìyàn sanra jù nígbà tí atọ́ka ibi-aratí àwon dókítà òyìnbó pè ní bmi ju ọgbọ̀n30 lọ nínú ara isanra púpò kìí dédé wáyé lásán bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé isanra púpọ̀ jù lè fàá kí ọ̀rá ó dí àwọn fọ̀rán iṣan tí a mọ̀ sí ártìrì tí ó ń gbé ẹ̀jẹ̀... |
noble igwe noble igwe3 october 1984jẹ blogger nàìjíríà ti a mọ fun ifilọlẹ ere idaraya 360 group pẹlu tonia soares ati oye akdeinde |
joeboy joseph akinwale akinfenwa-donus 21 may 1997 ti a mọ ni ọjọgbọn bi joeboy jẹ akọrin naijiria mr eazi ti aami igbasilẹ empawa africa ṣe awari rẹ ni ọdun 2017 iru orin rẹ jẹ ti afro pop ati rb o je omo ilu eko ni naijiria iṣẹ mr eazi korin fàají with joeboy on october 26 2018 o de lo ipin rẹ ti ẹbun ti o gba lati e... |
franca gbodo frança pamiendi gbodo ojo ibi 1982 je asagbara omobirin orile ede nigeria ti oun dije ni igun 58 kiloti osi n soju orile ede nigeria ni ibi idije agbaye o kopa ni olympic ti igba eerun ti odun year 2000ni igun ti 53kilo ati niolympic ti igba eerun ti odun 2004 ni igun 58 kilo o kopa ni idije agbaye ni aipe... |
temi otedola temiloluwa elizabeth otedolaojoibi 20 march 1996 je oserebirin omo orile-ede naijiria ati pe o tun je onka bulọọgi arabinrin naa ni olokiki fun ipa moremi oluwa ninu fiimu citation 2020 eto eko o kọ ẹkọ itan aworan ni university college london university of london ise otedola bẹrẹ bulọọgi aṣa kan ti a pe n... |
femi otedola femi otedola ojobi 4 osu kokanla odun 1962 je onisowo orile-ede naijiria oninuure ati alaga tele fun forte oil plc lówọ́lówó ó jé álágá geregu power plc igbesi aye ibere wo bi otedola ni ilu ibadan olu ilu ipinle oyo guusuiwoorun naijiria ninu idile oloogbe sir michael otedola gomina ipinle eko lati 1992 s... |
lalisa manoban |
victoria university of manchester |
umaru abdullahi umaru abdullahi born november 30 1939 jẹ́ adájọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ààrẹ tẹ́lẹ̀ ti àwọn ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ní nàìjíríà íse rẹ gẹgẹ bí olófin justice umaru was call to the bar ni ọdún 1968 a sì yàn gẹgẹ bí ọkan lára àwọn alága nigerian courts of appeal ni ọdún 1983 gẹgẹ bí adájọ ni odún 1987... |
ọrọ ìṣe |
ede boga ede boga tabi boka je ede afro-asiatic ti won n so ni ijoba ipinle adamawa ti orile-ede naijiria |
tubokosemie abere tubokosemie abere abi ni ojo kejidinlogun osu kejo odun 1950 je olori alufa ni ijo anglican ni naijiria ti o ti feyinti o je olori alufa ni okrika ikan ninu mesan ijo anglica ni igberiko ti niger delta o si je ikan ninu merinla ninu ijo naijiria won yaa soto gege bi asaaju olori alufa ni okrika ni ijo... |
ilera eko ilera eko ni ètò ìlera tí ìjọba èkó gbé kalẹ̀ lábẹ́ ilé-iṣẹ́ lagos state health management agency lashma láti lè jẹ́ kí tẹrú-tọmọ tólówó ti mẹ̀kúnù lẹ́sẹ̀ kùkú ó jẹ mùkútùn ètò ìlera tó péye pẹ̀lú owó pọ́ọ́kú ìjọba ìpínlẹ̀ èkó tún gbé ìgbésẹ̀ láti ṣí ẹ̀ka ètò ìlera yí káàkiri gbogbo agbègbè ìpínlẹ̀ èkó iṣẹ́ à... |
boga language boga ti a mo si boka je ede afro-asiatic ti a nso ni ipinle adamawa ti nigeria |
anglican diocese of aba ile ijosin anglican diocese ti ilu aba jẹ ọkan ninu mẹsan laarin awọn anglican province ti aba bishop lọwọlọwọ ni christian ugwuzor |
anglican diocese ti abakaliki the anglican diocese ti aba jẹ ọkan ninu mẹsan laarin awọn anglican province ti abakaliki bishop lọwọlọwọ ni monday nkwoagu |
monday nkwoagu monday chukwuma nkwoagu jẹ biṣọọbu anglican ni naijiria o jẹ bishop lọwọlọwọ ti abakaliki ọkan ninu awọn mejila laarin ẹkun anglican ti enugu |
anglican diocese ti abuja anglican diocese ti abuja je okan ninu awon 13 laarin awon anglican province ti abuja bishop lowolowo ni archbishop henry ndukuba won tun je primate ti awon church of naijiria |
anglican diocese ti afikpo anglican diocese ti afikpo je okan ninu mesan laarin awon anglican province ti enugu bishop lowolowo je paul udogu |
paul udogu paul udogu jẹ́ bíṣọ́ọ́ọ̀bù ìjọ anglican ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì jẹ́ bíṣọ́ọ́ọ̀bù ti ẹ̀ka afikpo láti ọdún 2010 |
anglican diocese ti akoko edo anglican diocese ti akoko edo jẹ́ ọ̀kan nínú mẹ́sàn án láàrín àwọn ẹ̀ka ìjọ anglican tí ó wà ní bendel bíṣọ́ọ́bù tó ń darí lọ́wọ́ níbẹ̀ ni jolly ehigiator oyekpen |
ilé ìfowópamọ́ ilé ìfowópamọ́ je ile-ise ti a daa sile lati gba owo wole san owo jade tabi ya awon onibara lowo fun idokowo |
endangered languages in nigeria èdè ìlú nàìjíríà tí owá ni ijamba láti parunmọ́kàndínlọ́gbọ̀n nínú àwọn èdè kékèké ilẹ nàìjíríà ni ọ ti parun mokandinlogbon omin ni o ti wa ni bèbè lati parun mẹ́ta nínú àwọn èdè agba ni nàìjíríà - èdè yorùbá èdè ìgbò ati ede itshekiri ni àwọn náà ti wa ninú ewu láti parun gẹ́gẹ́ bíi ìw... |
valentine ọjọ valentine ti wọn tun pe ni ọjọ saint falentaini tabi ajọdun falentaini ma n waye lọdọọdun ni oṣu keji ọjọ kerinla o pilẹṣẹ gẹgẹbi ọjọ ajọdun kristiẹni ti o bu ola fun ọkan tabi meji awọn ajẹriku kristiẹni akọkọ ti a npè ni saint valentine nipasẹ aṣa eniyan oti di asa pataki ẹsin ati ayẹyẹ ife ni ọpọlọpọ a... |
agbassa agbassa ni oruko okan ninu awon ijoba urhobo meji to wa ni ijoba ibile warri south delta state nàìjíríà ekeji ni okere-urhobo orukọ 'agbassa' jẹ ti ilu brítánì ti o wa lati orukọ atilẹba rẹ 'agbarha' eyiti o tun wa ni lilo ọba ti o wa lọwọ ni hrm orhifi ememoh ii awujo agbegbe meje lo wa ti o jẹ ijọba agbarha a... |
shrek shrek jẹ fílmu ti ere idaraya ará amẹ́ríkà |
tobi bakre nigerian actor tobi bakre tí a bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹfà ọdún 1994 jẹ́ òṣèré tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì jẹ́ aláwòṣe olùgbàlejò ètò lórí ẹ̀rọ agbóhùn-mámōrán àti a yàwòrán tobi di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kọ́pa nínú ètò big brother naija ẹlẹ́kẹ̀ẹta tí ó sì yege ní ọdún 2018 ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.