raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
tobi bakare |
fúnkẹ́ akíndélé |
rónkẹ́ òdúsànyà |
kúnlé afọláyan |
rónkẹ́ òjó |
wùnmí toríọlá |
lọlá àlàó |
murphy afọlábí |
láídé bákàrè |
adéyẹmí afọláyan |
àrẹ̀mú afọláyan |
mojí afọláyan |
razaq ọláyíwọlá |
gabriel afọláyan |
àìná gold |
lọlá margaret |
fausat balógun |
accountant general of the federation accountant general of the federation jẹ́ olùṣàkóso ti ilé-ìṣura ti orílẹ̀-èdè federal republic of nigeria àrẹ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ló máa ń yan olùṣàkóso yìí sípò láti sìn fún ọdún mẹ́rin pẹ̀lú ìṣàkóso tí ìwé-òfin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọdún 1988 ni wọ́n dá ọ́fíísìì yìí sílẹ̀ lábẹ... |
áìshà bùhárí |
ọjọ́ ayẹyẹ ìgbòmìnira ní orílẹ̀-èdè gambia 1965 ofin ominira gambia 1964 1964 c 93 jẹ ofin ti ile-igbimọ aṣofin ti united kingdom ti o funni ni ominira fun gambia pẹlu ipa lati 18 kínní 1965 |
ayẹyẹ ìgbòmìnira |
òògùn oogun jẹ eyikeyi nkan yato sí óúnjẹ ti ó sé lò fún itọju tabi imularada àìlera tàbí aìsàn a lè lo oogun nipa fi fíi simu di dajegbí gbémì abere ati béèbè lo |
oúnjẹ óúnje jẹ ohunkohun ti a le je tabi mu lati fun ara ni okun ounjẹ ma ún saba nií àmúaradàgbà carbohydrate ọra ati awọn oun ìsara lóore miiran ti ó se pataki fún itoju ara àti agbára tí ó ye a ma un saba ri ounje ni ara ewéko eranko tàbí elufungi o si ma un lilo yíyí padà láti so di nkan tí o sé je ounje kií se fún... |
hålo brian wadley ti a mọ nipasẹ orukọ ipele rẹ halo ti a ṣe si hålo jẹ akọrin akọrin ati akọrin lati detroit michigan amẹrika |
halo |
david nnaji david nnaji a bi ni oṣù keje ọdún 1985 jẹ òṣèré fíìmù nàìjíríà àti onkọwe ọmọ ilẹ nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ àti ẹkọ rẹ a bí nnaji ni oṣù keje ọdún 1985 ni ìpínlẹ̀ èkó ní ilẹ̀ nàìjíríà ìlú èkó ni o ti lọ sí gbogbo ilé ìwé tí o lọ |
wande coal oluwatobi wande ojosipe tí a bí ní ọjọ kejidinlogun oṣù kẹwàá ọdún 1985 tí orúkọ ìnagijẹ rè ni jẹ wande coal jẹ́ ọ̀kọrin ti orílé èdè nàìjíríà àti akọ-o ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ ayé àbí wande coal ní ọjọ́ kejilelogun oṣù kẹwàá ní erékùṣù èkó ní ìpìlè èkó ní orílè-èdè nàìjíríà orúkọ bàbá rẹ ń jẹ́ olóyè ìbùkún olúfúntọ́... |
oyún oyún jẹ́ àkókò tí ọ̀kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ọmọ tí ń dàgbà sínú ilé-ọmọ obìnrin oyún púpọ̀ kan máa ń jẹ́ ju ọmọ kan lọ gẹ́gẹ́ bí ìbejì oyún máa ń wáyé nípasẹ̀ ìbálòpọ̀ ṣùgbọ́n ó tún lè wáyé nípasẹ̀ àwọn ìlànà ìrànlọ́wọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ láti gbáyán mì oyún lè já sí ìbímọ láàyè ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó wáyé nígbà tí oyún bá jábọ́ lára o... |
up north up north jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí ó jáde láti ọwọ́ anakle films and inkblot productions ní ọdún 2018 ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ditope oshin ṣe olùdarí rẹ̀ naz onuzo and bunmi ajakaiye ló kọ ire náà látàrí itan tí editi effiong kọ ní ìlú bauchi ni wọ́n ya iṣẹ́ náà pẹ̀lú yíya ọ̀sẹ̀ kan ní ìlú èkó lagos |
queen's college lagos queen's college lagos jẹ́ ilé-ìwé gírámà ìjọba tí ó wà fún àwọn obìnrin nìkàn ilé-ìwé yìí wà ni yàbá ìpínlè èkó orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì ní àwọn ohun èlò ibùgbé fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ọjọ́ kẹwàá oṣù ọ̀wàwà ọdún 1927 nígbà tí nàìjíríà ṣì wà lábẹ̀ àwọn òyìnbò amúnisì ni a dá ilé-ìwé yìí sílẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyà... |
frank donga nigerian actor and comedian kúńlé ìdòwú tí orúko ìnagije rẹ̀ jẹ́ frank donga jẹ́ òṣèré àti apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣe eré kan lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ the interview ní ndani tv eré yìí jẹ́ eré apanilẹ́rìn-ín tó dá lórí awáṣẹ́ aláìbìkítà kan nípasẹ̀ yìí wọ́... |
naeto c naetochukwu chikwe tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ naeto c jẹ́ rápà ti orílẹ̀-èdẹ nàìjíríà olórin afrobeat àti aṣagbátẹ́rù rẹ́kọ́ọ̀dù ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ìlú houston ní texas ni wọ́n bí i sí àmọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ni gómínà ìpínlẹ̀ imo emeka ihedioha yan naeto c láti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ nígbà tí ó wá sí ipi... |
ayo makun ayodeji richard makun tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ay jẹ́ òṣèré ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà apanilẹ́rìn-ín òńkọ̀wé olóòtú àti olùdarí eré ó sì máa ń ṣe ètò lórí rédíò àti lórí ẹ̀rọ̀ amóhùn-máwòrán ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1971 ni a bí ayo ìlú ifon ti ìjọba ìbílẹ̀ ose ní ìpínlẹ̀ òndó ni ó ti wá òun ni ag... |
afang soup obe afangi ti a ko gbodo sipe ni obe okazi tabi obe ukazi obe ti awọn ti o wa ní ìyá gúúsù-iwo oorun ile naijiria je obe ti o ṣẹda lati ọdọ awọn efiki ni ìpínlẹ̀ cross river ati awọn ibibio ni ìpínlẹ̀ akwa íbọm ni ìyá gúúsù ilẹ nàìjíríà o jẹ oúnjẹ ti oni okiki gidigan ni ile nàìjíríà àti àwọn apá kankan ni a... |
ay makun |
naeto c |
30 days in atlanta 30 days in atlanta jẹ́ fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jáde ní ọ̣dún 2014 ó jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín tí patrick nnamani kọ tí ayo makun ṣe agbátẹrù rẹ̀ tí roberts peters sì jẹ́ olùdarí fíìmù náà ipinle eko àti ìlú atlanta ni a ti ya fíìmù ọ̀un tí ó sì jáde fún wíwò ní sinimá ni ọjọ́ kọkànl... |
ilé-ọmọ ilé-omo jẹ́ èyà ara obìnrin tàbí abo eranko nínú èyi tí ọmọ inú ma ń dàgbà sí tí ó sì ma ń rí oúnjẹ àti àwọn nǹkan míràn tí ó nílò kí ó tó di ìgbà ibí ilé-ọmọ jáde sí ojú ara obìnrin eléyìí jẹ́ ọ̀nà tí ọmọ ma ń gbà jáde nigba ìbí nígbà tí ìyá bá lóyún ilé ọmọ ma ń tóbi si láti gba ọmọ bí ọmọ bá ṣe ń tóbi si ní ... |
robert peters robert peters tí wọ́n tún máa ń pè ní roberts o peters jẹ́ òṣèré fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè naijiria aṣagbátẹrù eré olùyàwòrán àti alóhunlóyìn òṣèré ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣagbátẹrù fíìmù kan ní ọdún 2014 tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ breakout30 days in atlanta shades of attractions 2015 boxing day 2016 àti a t... |
ogba agodi ogbá agodi jé ibi àpéwò ní ìlú ìbàdàn ní orílè èdè nigeria a tún mò ó si ogbà ewéko àti igi ìgbé ogbà agodi ní ìlú ìbàdàn fi ìdí solè sí oríi àádòta lé l'ógòrún ékà itan teletele ni a n pe ni ogba eranko ati igi igbe ni odun 1967 ni a da ogba agodi sile ijamba omiyale ti ogunpa ba ogba naa je ni odun 1980 ti... |
majid michel majid michel tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógójì oṣù kẹsàn-án ọdún 1980 jẹ́ òṣèré ti orílẹ̀-èdè ghana olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ̀ amóhùn-máwòrán ajíhìnrere àti oníwà-ìranmọlàkejì-lọ́wọ́ wọ́n yàn án fún ìdíje gbígba àmì-ẹ̀yẹ fún òṣèré-kùnrin tó dára jù lọ ní ayẹyẹ africa movie academy awards ní ọdún 2009 2010 2011 2012 ... |
karlie redd karlie redd née lewis tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹrin ọdún 1974 tí wọ́n sì sọ ní keisha lewis jẹ́ gbajúmọ̀ lórí ètò lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan lórì ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ní orílẹ̀-èdè amerika ó tún jẹ́ òṣèré àti olórin |
áljẹ́brà |
àsà ìwé kíkà ìwé kíkà àsà iwé kíkà se pàtàkì nítorí pé ó je ìpìlè fún imo ati ìserere ninu eko kiko pelu aniyan l'orisisrisi ti o je mo mimo ko ati mimo ka opolopo orlleede ni o ti gbaju mo eto ilana iwe kika ti o yaranti ni ida keji asiko ti nkan ba din ku je asiko ti nkan naa ba ti n baje diedie tabi ti o ti fe ku bi... |
michael babatunde olátúnjí nigerian percussionist michael babatunde olatunji april 7 1927 april 6 2003 oje onílù nàìjíríà olukọni alapon nínú awujọ ati olorin kutukutu ayé rẹ olatunji jẹ ọmọ bíbí ìlú ajido ni èbá badagry lagos state ni guusu iwọ-oorun nigeria ọkàn lára ogu people a ṣe àfihàn olatunji sí orin ìbílẹ̀ ní ... |
èjè èjè jé ìsànfluid tí o má ún sàn káà kiri inú ara láti fún ara ní okun oxygen àti àwon nkan míràn tó wúlò fún ara èjè kún fún orisirisi nkan tí ara nílò bi homonu okun seeli funfun inú èjè seeli pupa inú èjè àti be be lo pilasimatí ódà bí omi àti àwon seeli èjè bí seeli èjè funfun seeli èjè pupa àti platelet ló para... |
kyiv |
orílẹ̀-èdè ìṣọ̀kan àwọn ìpínlẹ̀ amẹ́ríkà |
ìpínlẹ̀ kánò |
kunle odunlami nigerian footballer kúnlé ọdúnlamí tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù ẹrẹ́nà ọdún 1990 jẹ́ ọ̀gbọ́ǹtarìgì abábọ́ọ̀lù nàìjíríà tí ó jẹ́ dìfẹ́ẹ́dà fún gokulam kerala fc |
kunle remi kúnlé rẹ̀mí wọ́n bi ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1988 | orúkọ ìbí- oyèkúnlé ọpẹ́yẹmí olúwarẹ̀mí jẹ́ òṣèré nàìjíríà tí wọ́n mọ̀ ọ́ fún àwọn ipa ribiribi rẹ̀ ní falling family forever and tinsel ó di olókìkí lẹ́hìn ìgbà tí ó borí ìgbà kéjẹ tí wọ́n ṣe gulder ultimate search ní ọdún 2010 ó parí láti new y... |
ikechukwu uche ikechukwu uche wọ́n bi ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kìíní ṣẹrẹ ọdún 1984 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù nàìjíríà tó gbá bọ́ọ̀lù ní ìpò iwájú sítíráíkà tí wọ́n mọ̀ fún eré-ìtakìtì fún ayẹyẹ òpin bọ́ọ̀lù rẹ̀ uche gba bọọlu fun naijiria ni africa cup of nations |
william kumuyi nigerian clergyman olùṣọ́ àgùntàn william folorunsho kumuyi tí òpòlopò ènìyàn mò sí pastor kumuyi tàbí oluso agutan kumuyi ni olùdásílè àti alabojuto ìjo deeper life bible church gbogbo àgbáyé william kumuyi jé omo abínibí ìpínlè osun ní orílè-èdè nàìjíríà abí william kumuyi ní ìlú orunwa ìpínlè ogun ní ... |
aso villa aso villa jé ilè ibùgbé fún ááre orílè-èdè nàìjíríà láti odún 1991nígbà tí olori ologun ibrahim badamasi babangida so ìlú abuja di olú ìlú nàìjíríà aso villa wa ní ìlú abuja àwon olùgbé re si ni àárè muhammadu buhari àti idile rè kíkó aso villa bere ni ojo ketala osu kewa odún 1989 ásì pari kíkó rè ní ojo kin... |
elijah abina elijah oludele abinabi i okudu 16 1935 je pasito ati agba aguntan ti the gospel faith mission international gofamint ibere aye elijah ogundele abina ti wo bi sinu ile pa abraham akowanu abina ni aradagun badagry ipinle eko aye ara eni pastor abina gbe felicia abina ni iyawo ni osu keta ojo 30 odun 1966 pap... |
ikechukwu uche |
kunle remi |
vivica a fox american actress and producer vivica anjanetta fox ti a bi ni ojo kogbon osu keje odun 1964 je osere ti orile-ede amerika olootu fiimu agbelewo ati eleto lori ero amohunmaworan fox bere ise to yan laayo lori soul train ni odun 1983 si odun 1984 leyin igba naa o bere si ni maa se awon fiimu ogoji iseju lori... |
margaret bandele olayinka margaret bandele olayinka a bi ní ọjọ kẹrinla oṣù kẹsán ọdún 1958 tí gbogbo àwọn èèyàn mọ sí iya gbonkan jẹ òṣèré obìnrin onitiata ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà |
ikechukwu kalu nigerian footballer ikechukwu kalu ti won bi ni ojo kejidinlogun osu kerin ni 1984 je agbaboolu naijiria to gba boolu gege bi olutayo oruko e ikechukwu tunmo si agbara oluwa” ise re bii a-gba-boolu o bere ise e ni jasper united ni nàìjíríà o tewo bowe pelu uc sampdoria ni summer 2002 leyin to gba fun ako... |
awon ara ṣainiisi ni ile naijiria awọn ara ṣáínà ni ile naijiria awọn ara ilu ṣáínà ti n gbe ni naijiria pọ gidigan lara sì jẹ awon ṣáíniisi ti wọn bí sí naijiria pelu irandiran hakka itan iṣiwa sí ilẹ nàìjíríà ni ọdún 1930 a ka awọn ṣainiisi pẹlu iran hakka mẹrin ti n gbe ni ile nàìjíríà awọn oniṣowo ti ilu hongi kong... |
the gospel faith mission international the gospel faith mission international gofamint je ijosin kristiani pataki kan ni naijiria ti reuben akinwalere george bẹrẹ ni yaba} ni 1956 the gospel faith mission international wa ni opolopo orile-ede gege bi britain ati awon united states |
homonu homonu jẹ kemikali ti àwon glandì kòkan ninú ara n se láti fofin si isé seeli àti àwon eya ara kòkan èjè tàbí ìsànfluid ara lóma ún gbé homonu láti ìbí tí a ti sé ló sí ibi tí o ti ma sisé homonu le fofin sí bí ènìyàn tàbí eranko se ún dàgbà jeun wúwà tàbí sun nígbà ti okunrin bá ún balaga homunu ni oun mú kí oh... |
paulette goddard paulette goddard ti orúkọ abisọ rẹ jẹ marion levy gbé ayé lati ọjọ kẹta oṣù kẹfà ọdún 1910 titi dé ọjọ ketalelogun oṣù kẹrin ọdún 1990 o jẹ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà |
daniel fagunwa |
hubert ògúndé |
omi ọ́mú omi omútí àwon ènìyàn tún mò sí omi oyàn jẹ́ omi tí ó ma ń jáde nínú omú aláboyún tàbí ìyá tí ó ń fún ọmọ lọ́yàn omi omú jẹ́ orísun okun gbòógì fún ọmọ titun ó sì ní gbogbo èròjà tí omo nílò láti dàgbà àwọn èròjà bi omi carbohydrate aramuaradagba àti òrá omi ọmú sì tún ní àwọn eroja tó ma ń bàrùn jà nínú ara o... |
mount zion faith ministries mount zion faith ministries jé isé iranse eré ìtàgé tí a ti owo evang mike bamiloye àti gloria bamiloye dálè ní odun 1985 ète dídá isé iranse na kalè nigege bi olùdásílè mike bamiloye sé so láti se isé ihinrere kari aye àti láti sé igbero ìjo olorun ní ojó kokanla osù keje odun 1986 isé iran... |
tilburg tilburg jẹ ìlú kàn ní gúúsù tí orílẹ̀-ède netherlands o fẹ́rẹ̀ tó ènìyàn eègbá lè ní ọkẹ mọ̀kanla 222000 tó ngbé níbẹ 2021 tilburg ní òkìkí nítorí schrobbeler rẹ tó jẹ́ ọtí líle tó wà fún mímú ni tilburg bákan náà ilé-ẹ̀kọ́ gíga tilburg wa níbẹ |
èdè jẹ́mánì |
kayode kasumi nigerian movie director káyọ̀dé kásúmì jẹ́ atọ́kùn àti alákòóso fún fíìmù àti vídíò orin ní nàìjíríà |
handman handman jẹ ilẹ nlá onigi ní manchester ní orílẹ̀-èdè england o jẹ ọkàn lára awọn ilẹ onigi diẹ tí o ṣẹku ni united kingdom |
dj snake french record producerwilliam sami étienne grigahcine wọ́n bi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 1986 tí wọ́n mọ orúkọ-ìtàgé rẹ̀ ní dj snake jẹ́ atọ́kùn rẹ́kọ̀dù faransé ó àkọ́kọ́ rí ìfojúsí lára láàgbáyé ní ọdún 2013 láti ara wí pé ó ṣe ohun-èlò ajẹmórìn tí ó ní ṣe pẹ̀lú àgbègbè rẹ̀ tó dá ní tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ... |
whatsapp whatsapp jé ikanni ibanidore lori èro ayelujara o gba àwon olumulo rè láyè lati fí òrò ranse si arawon ó sì tún sé fi se ipe fidio a lè ló ìkànnì ibanidore whatsapp lori foonu komputa tábìlì àti komputa alagbeka jan koum àti brain actonàwon mejeji jé alabasise yahoo télèrí lódá whatsapp kalè ní odun 2009 kí fa... |
kang young - hoon kang young-hoon o gbè ayé ni oṣù kàrún ọjọ ọgbọn ọdún 1922 sí oṣù kàrún ọjọ kẹwàá2016 o jẹ àgbà olóṣèlú ni orilẹ ède south korea kan o jẹ alákòóso àgbà tí orilẹ ède south korea láti ọjọ kàrún oṣù kejìlá ọdún 1988 títí di ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣù kejìlá ọdún 1990o tún jẹ adele alákòóso mínísítà títí di ọj... |
rafeal pereira da silva rafeal pereira da silva a bi ni ọjọ kẹsan oṣù keje ọdún 1990 jẹ ọmọ orílẹ̀-èdè brasil iṣẹ́ bọọlu afẹsẹgba lọ n ṣe o tún gbà bọọlu fún ikọ manchester united ní orílẹ̀-èdè england |
ere-idaraya abele ere-idaraya abele jẹ ọpọlọpọ awọn ere eleto tabi awọn adaṣe ti ara idije ti a ṣe ni igba gbogbo boya ni ile ni ile ti o ni aabo daradara tabi ni ibi isere ere ti a ṣe ni pataki gẹgẹbi ibi- idaraya kan omi-iluwe gbagede tabi pápá ìṣeré ti orule kan <ns>10</ns> <id>16733</id> <revision> <id>534273</id> ... |
sibi sibi je oun elo oninu kodoro ti oni ibi agbamu lati firo nkan ati latifi jeun abi mimu |
foonu alagbeka foonu alagbeka jé telifoonu alagbeka jé óun tosé pataki pupo tiósì me anfaani papa julo latilo fun rirakata pelu awon oun ribiribi imiran tonse funwa lati mu igbesi aiye rorun funwa motorola ni ilé-ise tí o koko sé foonu alagbeka ní odun 1973 la ti igba na orisirisi foonu alagbeka tí wa kaka kiri lopolop... |
ẹ̀mi àìrí àwọn yorùbá gbàgbó pé ẹ̀mí áìrí méjì ni ó wà bí rere ṣe wà bẹ́ẹ̀ náà ni búburú náà wa wọn tún ní èrò pé oríṣi ẹ̀mí áìrí méjì ló wà àwọn òrìṣà ati àwọn òkú ọ̀run àwọn wọn èmi áìrí rere yìí ni ó máa ń ṣe àtilẹhin fún ènìyàn ní ojojúmọ́ ayé rẹ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn lé bínú sí ẹnikẹ́ni to bá kọ tàbí kùnà láti ṣe ... |
2022 2022 tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ sátidé nínú kalẹ́ndà gregori ọdún 2022 ni ó ṣáájú ọdun 2023 òun sì ni ó ló tẹ̀lé ọdún 2021 àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó sẹ̀ ní ọdún 2022 •ọjọ́ ìkejì oṣù kíní january 2 abdalla hamdok kọ̀wé iṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà àgbà fún orílẹ̀-èdè sudan lẹ́yìn ìwọ́de ńlá •ní ọjó keje oṣù kínní january 7 iye ... |
federal university of technology minna federal university of technology minna jé yunifásitì tí ìjoba ní minna ìpínlè niger ní orílè-èdè nàìjíríà a da kalè ni ojo kíni osù keji odun 1983 oruko olori alákókó ti yunifásitì na ní jo ndagi oruko olórívice chancellor tó wà lori oyè lowo ni ojogbon abdullahi bala àwon èka èkó... |
aṣọ aṣọ jé ohun tí ènìyàń ń wọ̀ láti bo ìhòhò oríṣi ohun èlò ni a fi ń hun aṣọ àwọn ohun èlò bíi òwú ọ̀rá awọ sílìkì àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ lẹ́yìn híhun aṣọ aṣọ tún nílò rírán kí ó tó le di wíwọ̀ yàtò sí fún bíbo ìhòhò aṣọ tún wà fún oge àti ìdánimọ àpẹẹrẹ oríṣi aṣọ ilé yorùbá ni ìró àti bùbá agbádá dànsíkí búbù kẹ̀mbẹ̀ àti... |
amúlétutù amúlétutù tàbí èro amúlétutù tí òpòlopò ènìyàn mò sí ac jé èro tí a fi ún mu ilé tùtù amúlétutù má ún lo kemikali tí a mò sí refrigerant láti fa ooru kúrò ni inú ilé apakan amúlétutù tí a mo sí condenser a sì ti oru na jade engr willis havilland ní o kókó se èro amúlétutù ní odun 1902 láti igba na òpòlopò ilé... |
indian premier league indian premier league ipl jẹ aṣaju-ija cricket ti awọn ọkunrin ti njijadu nipasẹ awọn ẹgbẹ mẹwa ti o da lori awọn ilu india mẹwa mẹwa ajumọṣe jẹ ipilẹ nipasẹ board of control for cricket in india bcci ni ọdun 2007 ni 2010 ipl di iṣẹlẹ ere idaraya akọkọ ni agbaye lati tan kaakiri lori youtube awọn ... |
clothing |
sarz nigerian record producer and musician osabuohien osaretin tí a bí ní ọjọ́ ketedilogun ọdún 1989 tí orúkọ inagije rẹ ń jẹ́ sarz jẹ ẹni tó ń gbé rẹkodi orin jáde ti a bí sì ìlú benin city edo state tí wọn sì mọ gẹ́gẹ́ bí gbajúgbajà sarz on the beat/reallyní ìbéèrè ati ìparí ere àgbéléwò lord of ajasa tí ó jáde ní ọd... |
skales nigerian musician raoul john njeng-njeng tí a bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹrin ọdún 1991 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ skales tí àpèja rẹ̀ ni seek knowledge acquire large entrepreneurial skills jẹ́ olórin tàkasúféé àti akọrin kalè tí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní ọdún 2000 ó bèrè sí ní ṣe àkọsílẹ̀ orin tàkasúféé ni ilu kaduna n... |
russo-ukrainian war ogun russo-ukrainian je ogun ti russiabelarus ati ukraine lowosi russia ati belarus l'egbe kan ati ukraine l'egbe miran rogbodiyan yii bere ni osu february 2014 leyin isote ti iyi leyin ti otun dojuko ipo crimea ati awon abala dobeas t'amo kariaye ni abala ti ukraine rogbodiyan pelu afikun crimea mo... |
òjògbón ojogbon jé ipò èkó tí o ga jù ní yunifásitì tàbí ilé-èkó miran àwon ojogbon ma ún jé oloye gíga/pupo ní aaye èkó won kí ènìyàn tó le di ojogbon o gbodo kókó keko láti di dokita tí ìmòyephd |
òjògbón abdulrasheed na'allah ọ̀jògbón abdulrasheed na'allah tí a bi ní ìlú ilorin ní ìpínlè kwara ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà a bi ní ojó kokànlélógún oṣù kejìládecember 21 ọdún 1962 òjògbón abdulrasheed ni olori ilé-ẹ̀kọ́ yunifásitì ìpínlè kwara láàárín ọdún 2009 sí ọdún 2019 ósì di olori ilé-ẹkọ́ yunifásitì ti ìlú àbújá ... |
yunifásitì ìpínlè kwara yunifásitì ìpínlè kwárà kwara state university tí àwon ènìyàn mo sí kwasu tí o kalè sí malete jé yunifásitì ìjoba ìpínlè kwara adá yunifásitì ìpínlè kwara kalè ní osù kokanlanovember odun 2009 óun ni yunifásitì karundinlogorun ti wọn da kalè ní nàìjíríà yunifásitì ìpínlè kan ní nàìjíríà òjògbón ... |
dokitaphd dokitaphd tí a tún mò sí dokita tí ìmò òye jé ara àwon ipò èkó tí o ga jù ní yunifásitì tàbí ilé èkó míràn o jé oyè-ekó tí ènìyàn ma ún sé iwádí tó dájú ní èka èkó rè tí o to le ri gba òpòlopò ipò akeko ní yunifásitì àti ilé-èkó giga olodun merin miran ní lò oludije akeko láti ní dókítá ìmò òye kí won tó le g... |
ọwọ́ ọwọ́ ni a lè pè ní ẹ̀ya ara tí fi ń di nkan mú tí ó si ni ọmọ-ìka púpọ̀ ní ìparí rẹ̀ òun ni ó sì kẹ́yìn ọrùn ọwọ́ a lè ṣalábàá-pàdé ọwọ́ lára àwọn ẹranko elégungun bíi ènìyàn ọ̀bọ ìnàkí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ọwọ́ ènìyàn sábà máa ń ní ìka mẹ́rin tí àtànpàkò sì ṣ'ìkarùn ún wọn àpapọ̀ gbogbo àwọn ọmọ ìka yí ni a ń pè ní... |
ile-iwe giga ile-iwe giga tí a tún mò sí ilé-èkó giga jé ile-iwe tí a ti ún kekoàti keko gboye léyìn ilé-ìwé sekondiri gbòógì orisi meta ilé-èkó ni ówà ní nàìjíríà ilé-èkó yunifásitì polytechnics àti college ti education yunifásitì fún akeko gboyè ní oyè básélòbachelor degree polytechnic fún akeko gboyè ní oyè diploma ... |
ilé-ìwé sekondiri ilé-ẹ̀kọ́ girama jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ọlọ́dún mẹ́fà tí ó kàn lẹ́yìn ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ilé-ẹ̀kọ́ girama ti ọ̀jẹ̀-wẹ́wẹ́ ọlọ́dún mẹ́ta akọ́kọ́ junior secondary nígbà tí ìkejì jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ girama ti àgbà ọlọ́dún mẹ́ta senior secondary lẹ́yìn ìpele ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ yí ní orílẹ̀-èdè nà... |
deeper christian life ministry ìjọ deeper christian life ministry tí a tún mò si ìjo deeper life jé ìjo onihinrere tí o olú rè kalè sí gbàgádà ìpínlè eko ní nàìjirià láti ọwọ́ pastor folorunso william kumuyieni tí o jé adari ijo náà dá ijo náà sílẹ̀ ní ọdún 1973 ìjo náà bere bí egbe ikeko bibeli pèlú àwon akeko meedogu... |
ìjọ deeper christian life ministry |
johnson suleman johnson suleman tí a tún mò sí aposteli johnson sulemantí a bí ní march 24 1971 jé omo bibi ìpínlè edo a bi sí ìlú benin ní ìpínlè edo nàìjirià a bi sínú idile tí musulumi léyìn ojó díè tí a bi awon woli wà si beninìlú tí a bi sí láti wá so fun òbí rè pé a ti bi omo tí yó je woli niwaju oluwa aposteli j... |
end sars end sars jé iwode ifehonuhan tí àwon odo nàìjirià láti fopinsi eka olópá orílè-èdè nàìjirià tí a mò sí sars àti láti fopinsi ìsì agbara lò eka olopa nàìjirià iwode ifehonuhan náà bèrè ní osu kewa 2020 ní ìgbà tí fiimu bí àwon olopa sars kan sé pa okurin kan farahan lórí ìkànnì ayelujara òpòlopò odo nàìjirià ni... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.