raw_text
stringlengths
2
128k
pope urban vi
pope sixtus iii
pope john x
pope pius vi
pope benedict ix
pope stephen iv
pope clement ii
pope nicholas ii
pope leo vi
pope john xi
pope felix iii
pope paschal i
pope leo vii
pope innocent vi
pope gregory xi
pope callixtus ii
pope innocent xii
pope anastasius iii
pope anastasius ii
pope anastasius i
pope alexander viii
pope innocent xi
pope gregory xv
pope marinus ii
pope paul v
pope innocent ix
pope gregory xiv
pope marcellus ii
pope julius iii
pope leo x
pope agapetus ii
ipa tí àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà ti ọdún 2019-2020 ní sí àwùjọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàm̀bá tí ó wáyé látipasẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà ti ọdún 2019-2020 ti nípa rẹpẹtẹ lórí agbèègbè àti bójú ọjọ́ ṣe rí ìdínkù nínú àwọn ìrìn àjò ojú òfuurufú ti mú kí àwọn ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ dínkù gan-an ìsémọ́lé àti àwọn ìlànà mìíràn tí wọ́n ṣàmúlò ní ìlú...
àrùn tó máa ń ràn ọlọ́jẹ̀ jẹ́ kòkòrò kékeré tí a kò lè rí pẹ̀lú ojú lásán tó sì lè fa àìsàn tàbí àárẹ̀ sára èèyàn a tún máa ń pè é ní kòkòrò tàbí arọ̀n kékeré nítorí ara olùgbàlejò rẹ̀ ló ti máa ń jẹun ọlọ́jẹ̀ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ ni fáírọ́ọ̀sì àti bakitéríà àwọn àìsàn tó má ń fà jẹ́ èyí tó le ran ni tó sì máa ń tàn ká cov...
wikipedia yorùbá
katja seizinger katja seizinger jẹ́ ògbóntagì eléré ìdárayá orí yìnyí ọmọ orílẹ̀-èdè russia
oke olumo
olumo rock
ọlagunsoye oyinlọla
ìgba òṣèlú èkejì nàìjíríà
àìsàn inú afẹ́fẹ́ àìsàn inú afẹ́fẹ́ tàbí atẹ́gùn jẹ́ àìsàn kí àìsàn tí kòkòrò afàìsàn lè fà tí ẹ̀rún rẹ̀ nínú atẹ́gùn lè ṣàkóbá fún ẹlòmíràn bí wọ́n bá mí í sínú ògùn irú àìsàn báyìí ṣe pàtàkì sí ènìyàn àti ẹranko àwọn kòkòrò afàìsàn náà lè jẹ́ kòkòrò ààrùn-ẹ̀ràn bakitéríà tàbí fọ́nńgaì tí wọ́n lè ràn káàkiri nípa èémí...
ẹ̀tọ́ ìbò gbogbo ènìyàn
ẹ̀tọ́ ìbò fún gbogbo ènìyàn ẹ̀tọ́ ìbò fún gbogbo ènìyàn ṣe ẹ̀tọ́ ìdìbò fún gbogbo ọmọ ìlú tó jẹ́ àgbàlagbà láìkàsí ọlà ìpawọ́ akọmbábo ipò láwùjọ ẹ̀yà ènìyàn ẹ̀yà èdè tàbí ìdínà míràn
universal suffrage
xhosa people
àwọn ẹ̀yà xhosa style=background-color #b0c4de | èdè xhosa style=background-color #b0c4de | ẹ̀sìn traditional african religions christianity style=background-color #b0c4de | ẹ̀yà abínibí bíbátan zulu hlubi swati and southern and northern ndebele people àwọn ẹ̀yà xhosa pípè ní yorùbá bíi kósà ni ẹ̀ka ẹ̀ya àwọn bantu tó ...
àyẹ̀wò àìsàn àyẹ̀wò àìsàn jẹ́ ìgbésẹ̀ tàbí ọ̀nà kan tí àwọn oníṣẹ́ ètò ìlera ma ń gbà láti fìdí òdodo àrùn tàbí àìsàn múlẹ̀ ní ara ènìyàn tàbí ẹranko kí wọ́n lè mọ irúfẹ́ oògùn tí wọn yóò lò si kí àláfíà aláàrẹ̀ náà ó lè padà sípò àwọn ohun tí wọ́n nílò láti fi ṣe àyẹ̀wò ni ìṣẹ̀lẹ̀ àtéyìnwá àti ìtan nípa ìlera aláàrẹ̀ ...
àjàkáyé-àrùn àjàkáyé-àrùn pandemia láti inú èdè greek tó túnmọ̀ sí gbogbo àti ènìyàn jẹ ìbújáde àkóràn àrùn kan ti o nlọ kaa kiri orílẹ̀-èdè tàbí ẹkùn tí ó ju ẹyọkan lọ yíyára tànkálẹ̀ àrùn laarin ọ̀pọ̀ ènìyàn ní agbegbè tàbí ẹkùn fún ìwọ̀nba ìgbà diẹ ni wọ́n npe ni àjàkálẹ̀-àrùn epidemic ìtànkálẹ̀ àrùn tí ó jẹ́ wípé o...
ajakale-arun tokari-aye
aṣọ-ìbòjú nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn káríayé ẹ̀rànkòrónà ọdún 2019 use of face coverings during the covid-19 pandemic onírúurú abá lórí wíwọ ìbòjú nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn káríayé ẹ̀rànkòrónà ọdún 2019 láti ọwọ́ àwọn elétò àti àjọ ìlera àti àwọn ìjọba àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who àti àwọn elétò ìlera àwùj...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní gúsù sudan àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní gúsù sudan tí wọ́n tún ń dà pè ní covid-19 ni ó gbòde kan ní orílẹ̀-èdè sudan gúúsù ọjọ́ karùún oṣù kẹrin ọdún 2020 nígbà tí yóò fi di ọjọ́ kẹsàán oṣù keje wọ́n ti rí àkọsílẹ̀ iye ènìyàn tí ó tó ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùún kan ó lé mọ́kandínlọ́gbọ̀n tí wọ́n ...
àjàkálẹ̀-àrùn tókárí-ayé
pandemic
àjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019-2020
àjàkáyé-àrùn covid-19
grace oyèlùdé grace atinuke oyèlùdé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1931 november 16 1931 jẹ́ omidan tó rẹwà jùlọ àkọ́kọ́ lórílẹ̀ èdè nàìjíríà lọ́dún 1957
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 lórílẹ̀-èdè olómìnira benin àjàkálẹ̀ àrùn ẹ̀rànkòrónà-19 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí covid-19 kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè olómìnira benin ní oṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà covid-19 ni...
ìbẹ́sílẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 lórílẹ̀-èdè olómìnira benin
ìbúrẹ́kẹ́ àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní gúsù sudan
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní ilẹ̀ màláwì àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé ilẹ̀ màláwì ní́ ọjó kejì oṣù kẹrin ọdún 2020 ìpìlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ tí ó ń rí si ètò ìlera ní àgbáyé world health organization fìdí rẹ múlẹ̀ pé àrùn kòrónà ni ó fa àìsàn atégùn níbi àpéjọpọ̀ àwọn ènìyàn ní w...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní sàó tòmẹ̀ àti principe àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè são tomé àti príncipe lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 2020 the first death was recorded on 30 april bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrón...
ogun kírìjí ogin kírìjí tí a tún ń mọ̀ sí ogun èkìtì-parapọ̀ ni ogun abẹ́lé tí ó wáyé láàrín ẹ̀yà yorùbá fún odidi ọdún mẹ́rìndínlógún gbáko ogun yí wáyé lààrín ilẹ̀ ìbàdàn tí ó wà ní apá àríwá ilẹ̀ yorùbá ati ilẹ̀ ìjẹ̀ṣà ati gbogbo èkìtì pátá tí wọ́n wà ní apá ìlà-oòrùn ilẹ̀ yorùbá ohun tí ó fa ogun náà ohun tí ó fa o...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní mẹ̀lílà ongoing covid-19 viral pandemic in melilla spain wọ́n kọ́kọ́ kéde ìbẹ́sílẹ̀ àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní mẹ̀lílà lórílẹ̀ èdè spain lóṣù kẹta ọdún bí àrùn náà ṣe ń jàkálẹ̀ láti ìgbà dé ìgbà oṣù kẹta ọdún 2020 arákùnrin kan tí ó rìnrìn-àjò láti àgbègbè kan tí wọ́n ń pè ní iberian peninsula ...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní western sahara ongoing covid-19 viral pandemic in western sahara àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ní western sahara ní oṣù kẹrin ọdún 2020 àgbègbè tí orílẹ̀ èdè morocco pàṣẹ dé ní western sahara nìkan ni àrùn náà wà kò sí ní àgbègbè western sahara tí sahrawi arab democratic republicpàṣẹ...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní ceuta ongoing covid-19 viral pandemic in ceuta spain wọ́n kọ́kọ́ kéde àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní àgbègbè ní agbègbè ceuta lórílẹ̀ èdè spain ní oṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe ń jàkálẹ̀ láti ìgbà dé ìgbà oṣù kẹta ọdún 2020 arákùnrin kan láti àgbègbè kan ní orílẹ̀-èdè làìbéríà ló dé sí ceuta pẹ̀lú àmì...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ kóngò wọ́n kéde àrùn covid-19 àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ kóngò lọ́jọ́ lóṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà covid-19 ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọ...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní puntland ongoing covid-19 pandemic in puntland àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 kọ́kọ́ rápálá wọ puntland tí ó jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè somalia ṣùgbọ́n tí wọ́n dá dúró lọ́wọ́ ara wọn yàtọ̀ sí somalia gẹ́gẹ́ bí àwọn àjọ àgbáyé ṣe gbà wọ́n àpapọ̀ iye àwọn tí wọ́n ní àrùn covid-19 puntland lọ́jọ́ kejì...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní guinea ongoing covid-19 viral pandemic in guinea wọ́n kéde àrùn ẹ̀rànkòrónà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí covid-19 lórílẹ̀-èdè guinea lọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà covid-...
barakat quadre barakat oyinlomo quadre ọjọ́ìbí 1 may 2003 tàbí bárákátù oyinlọmọ kádírì jẹ́ oníṣẹ́ agbá tẹ́nìs ará nàìjíríà lọ́wọ́lọ́wọ́ òhun ní ará nàìjíríà tí ipò rẹ̀ gajùlọ ní ẹ̀ka ìdíje àwọn obìnrin ẹnìkan lórí wta ítí di 2024 2024 update óhun ni ó wà ní ipò kínní ní nàìjíríà ipò 9k ní áfríkà àti ipò 969 lágbàáyé n...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní madagascar ongoing covid-19 viral pandemic in madagascar wọ́n kéde pé ajàkálẹ̀ àrùn covid-19 bẹ́ sílẹ̀ lórílẹ̀-èdè madagascar lóṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà covid-19 ni ó ń fa àì...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè sudan àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè sudan jẹ́ ọ̀kan lára ìbúrẹ́kẹ́ àjakálẹ̀ àrùn kòrónà tí a tún mọ̀ sí kofid-19 tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé ohun tí ó ń ṣokùnfà àìsàn yí ni àrùn ọ̀fun àyà ati imú tí wọ́n ń pè ní bí àrùn kòrónà ṣe wọ orílẹ̀-èdè sudan àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí ...
ìbúrẹ́kẹ́ àjàkálẹ̀ àrùn kofid-19 ní orílẹ̀-èdè sudan
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè sudan
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní congo
covid-19
alberto fernández alberto ángel fernández tí a bí ní april 2 1959 jẹ́ olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ní báyìí ààrẹ argentina láti ọdún 2019 sí 2023
emmerson mnangagwa emmerson dambudzo mnangagwa m̩naˈᵑɡaɡwa ọjọ́ìbí 15 september 1942 ni olóṣèlú ará zimbabwe àti ààrẹ ilẹ̀ zimbabwe láti 24 november 2017 ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olóṣèlú zanupf àti igbákejì ààrẹ sí ààrẹ robert mugabe
àjàkáyé-àrùn covid-19 ní áfríkà lọ́jọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 2020 ni àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 kọ́kọ́ ṣẹ́yọ nílẹ̀ áfíríkà orílẹ̀ èdè íjíbítì ni ó sì ti kọ́kọ́ ṣẹ́yọ tí àkọ́kọ́ tí ó ṣẹ́yọ lápá iwọ̀-oòrùn áfíríkà ṣẹ́yọ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà púpọ̀ nínú àwọn tí wọ́n kó àrùn náà kó o láti ilẹ̀ òkèèrè ní europe àti orílẹ̀-èdè am...
hakeem jeffries hakeem sekou jeffries ọjọ́ìbí august 4 1970 ni olóṣèlú àti agbẹjẹ́rò ará amẹ́ríkà tó jẹ́ dídìbòyàn bíi aṣojú ilé àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà fún ìpínlẹ̀ new york láti ọdún 2013 ó jẹ́ ará ẹgbẹ́ dẹ́mókrátíkì
united states house of representatives
ilé àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ilé àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà the united states house of representatives ní èdè gẹ̀ẹ́sì ni ilé aṣofin kékeré ní kọ́ngrẹ́ẹ̀sì orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ilé àwọn alàgbà ni ilé aṣòfin àgbà lápọpọ̀ àwọn méjéèjì jẹ́ ilé-aṣòfin oníléìgbìmọ̀-méjì bicameral legislature fún orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà
2020 coronavirus pandemic in mali
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní málì àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè málì ní oṣù kẹta ọdún 2020 ìpìnlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù ìkíní ọdún 2020 àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ni àgbáyé world health organization fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn ẹ̀rankòrónà ni ó fa àrùn atégùn ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìlú wu...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè senegal ongoing covid-19 viral pandemic in senegal àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè senegal is jẹ́ ọ̀kan lára ìbúrẹ́kẹ́ àjakálẹ̀ àrùn kòrónà tí a tún mọ̀ sí kofid-19 tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé ohun tí ó ń ṣokùnfà àìsàn yí ni àrùn ọ̀fun àyà ati imú tí wọ́n ń pè ní severe acu...
oṣù kínní 29
festus onigbinde festus 'adegboye' onigbinde ọjọ́ìbí 5 oṣù kẹta 1938 ní modakeke ni olùkọ̀ bọ́ọ́lù-àfẹsẹ̀gbá ará nàìjíríà ó ṣe olùkọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ibi ìdíje ife-ẹ̀yẹ àgbáyé fifa 2002 kó tó di ìgbà yìí ó tún ti jẹ́ olùkọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù orílẹ̀-èdè nàìjíríà làrin ọdún 1982 àti 1984 ...
covid-19 pandemic
àjàkálẹ̀ àrùn covid 19 ní áfíríkà
covid-19 pandemic in africa
karl malone karl anthony malone ọjọ́ìbí 24 oṣù keje 1963 ni oníṣẹ́ agbábọ́ọ́lù alápẹ̀rẹ̀ ará amẹ́ríkà tó ti fẹ̀yìntì wọ́n mọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ the mailman ó gbá ipò power forward ó gbá bọ́ọ́lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù national basketball association nba pẹ̀lú utah jazz àti los angeles lakers
a faleye
mega 99
àjakálẹ̀-àrùn covid-19 ní bùrúndì àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè burundi àrùn kòrónà wọ orílẹ̀-èdè burundi ní ọjọ́ kínní oṣù kẹrin ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kí...
ogun ìṣojútùú ogun le túmọ̀ sí
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní àwọn erékùṣù kánárì wọ́n kéde àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní àwọn erékùṣù kánárì lọ́jọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdún 2020 nígbà tí àyẹ̀wò arìnrìn-àjò kan láti orílẹ̀-èdè jẹ́rmánì fihàn pé ó ní àrùn náà ni ilu la gomera ẹnikejì tí ó tún ní àrùn náà ni erékùṣù náà ni wọ́n kéde lọ́jọ́ kẹrìnlélógùn o...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní erékùṣù canari
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní central african republic ongoing covid-19 viral pandemic in the central african republic àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 bẹ́ sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè central african republic lóṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe ìbẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization who jẹ́rìí pé...
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní mauritania àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ni wọn fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè mauritania ní oṣù kẹta ọdún 2020 ìpìnlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé world health organization fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn ẹ̀rànkòrónà ni ó fa àrùn atẹ́gùn ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyà...
mòsámbìk
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orilẹ̀-èdè niger àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé ó ti tàn dé orílẹ̀-èdè olòmìnira niger nínú oṣù kẹ́ta ọdún 2020 àjọ amnesty international jábọ̀ rẹ̀ wípé àwọn kan fòfin gbé àwọn oníròyìn tí wọ́n ń kọ nípa àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè niger tí wọ́n sì ké sí ìjọba kí w...
àtòjọ àwọn obìnrin ẹnìkan ayọrí ìdíje wimbledon