raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
àtòjọ àwọn obìnrin ẹnìkan ayọrí open amẹ́ríkà |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orilẹ̀-èdè chad àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 dé orilẹ̀-èdè chad ní inú oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní ọdún 2020 tí wọ́n sì fìdí rẹ̀... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-9 ní kamẹrúùnù àjàkálẹ̀ àrùn covid-9 dé orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù ní inú oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní ọdún 2020 tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ mú... |
chiroptera ọlọ́wọ́-ìyẹ́ |
afọmúbọ́mọ |
mammalia |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní djibouti àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní djibouti wá nì ára àjàkálẹ̀-àrùn ẹ̀rànkòrónà 2019 covid-19 tí ó ń jà káàkíriayé èyí tí àrùn atẹ́gùn ẹ̀rànkòrónà 2 sars-cov-2 ń fà kòkòrò àrùn fáírọ́ọ̀sì yi tànkálẹ̀ dé orílẹ̀-èdè djibouti ní oṣù kẹta ọdún 2020 ìpìnlẹ̀ oríṣiríṣi àwọn orílẹ̀-èdè tí a mọ̀ gẹ́gẹ́... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní tógò àrùn covid-19 dé sí orílẹ̀-èdè togo ni oṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní ọdún 2020 tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ... |
àjakálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè cape verde àjàkálẹ̀ àrùn covid-9 dé orílẹ̀-èdè cape verde ní oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní ọdún 2020 tí wọ́n sì fì... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní kepu ferde |
àwọn ará georgia àwọn ará georgia ქართველები — ẹ̀yà ènìyàn ati orile-ede eniyan ni georgia |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní gàbọ̀n àjàkálẹ̀ àrùn covid-9 wọ orílẹ̀-èdè gabon ní inú oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní ọdún 2020 tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wí... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní eritrea àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè ẹritrẹ́à ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹta ìpìnlẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé world health organization fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn ẹ̀rànkòrónà ni ó ń fa àrùn atégùn ní àárín ọ̀pọ̀ ... |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè mozambique the àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní tàn kálẹ̀ dé orílẹ̀-èdè mozambique ní àárín oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní n... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní sámbíà àjàkálẹ̀ àrùn rùn covid-9 wọ orílẹ̀-èdè zambia ní inú oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní ọdún 2020 tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múl... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní zimbabwe àjàkàlẹ-àrùn ẹ̀rànkòrónà covid-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè zimbabwe ní oṣù kẹta ọdún 2020 àwọon agbègbè tí ó wà ní orílẹ̀-èdè zimbabwe ní pàtàkì àwọn bi i manicaland masvingo àti mashonaland tí ó wà ní ìla-òor̀ùn orílẹ̀-èdè zimbabwe paapa ti ń tiraka pẹ̀lú ìbújáde àrùn... |
ajàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní seychelles ajàkálẹ̀-àrùn covid-19 jẹ́ kíkóràn dé orílẹ̀-èdè seychelles ní oṣù kẹ́ta ọdún 2020 orílẹ̀-èdè seychelles ní àkọsílẹ̀ àwọn aláàrẹ̀ covid-9 tí iye wọn jẹ́ mọ́kànlá ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù karùún ọdún 2020 àwọn àsìkò tí ó ń ṣẹlẹ̀ oṣù kẹ́ta ọdún 2020 orílẹ̀-èdè seychelles kéde akọsílẹ̀ ajàká... |
bode akindele oloye bode akindele 2 june 1933 - 29 june 2020 jẹ onimọran ile-iṣẹ orilẹ-ede naijiria kan ati parakoyi ti ilu ibadanland ti apapọ iye oro re to 119 bilionu gẹgẹ bi iwadi ti ventures africa se ti won si gbe jade ni ọdun 2013 ninu iwe iroyin daily telegraph o je eni ikerindinlogun ti o lowo julo ni orile ed... |
lilian bach nigerian actress lilian bọlá bach jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀ṣẹ̀rè-bìnrin àti afẹwà ṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbé ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àti ìkẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí bọlá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí lilian ní erékùṣù èkó yorùbá ni màmá rẹ̀ tí bàbá rẹ̀ sìn jẹ́ ọmọ poland nítorí iṣẹ́ bàbá rẹ̀ ó gbé ní onírúurú ìlú lórílẹ̀ èdè nàìj... |
gabriel igbinedion olóyè gabriel osawaru igbinedion ọjọ́ìbí september 11 1934 ni oníṣòwò àti oníjóyè ará nàìjíríà láti ìlú ọkadá ní ìpínlẹ̀ ẹdó òhun ni ó wà lórí oyè gẹ́gẹ́bí esama ìlú benin |
ajàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní sierra leone ajàkálẹ̀-àrùn covid-19 tàn kálẹ̀ dé orílẹ̀-èdè ní orílẹ̀-èdè sierra leone ní ọjọ́ kọkanlélọ́gbòn oṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìl... |
armen sarkissian armen sargsyan arméníà ọjọ́ìbí 23 june 1953 ni olóṣèlú onímọ̀físíksì àti onímọ̀sáyẹ́nsì kọ̀mpútà tó ti wà lórí ipò bíi ààrẹ ilẹ̀ arméníà láti ọdún 2018 ó ti kọ́kọ́ wà ní ipò bíi alákóso àgbà ilẹ̀ arméníà láti ọjọ́ 4 oṣù kọkànlá ọdún 1996 títí di ọjọ́ 20 oṣù kẹta ọdún 1997 àti tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́bí aṣojú ilẹ̀... |
kamala harris kamala devi harris ọjọ́ìbí october 20 1964 ni olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ará amẹ́ríkà tó wà ní ipò gẹ́gẹ́bí alàgbà ilẹ́ aṣòfin orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà láti kalifọ́níà láti ọdún 2017 òhun ni wọ́n pè lórúkọ fún ipò ìgbákejì ààrẹ sí joe biden fún ẹgbẹ́ dẹmọkrátíkì nínú ìdìbòyan ààrẹ ọdún 2020 ní amẹ́ríkà |
ajàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè sierra leone |
ajàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè seychelles |
àjakálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè burundi |
alexander van der bellen alexander van der bellen ọjọ́ìbí 18 january 1944 ni ààrẹ ilẹ̀ austríà lọ́wọ́lọ́wọ́ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ó ti ṣiṣẹ́ bíi ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ọ̀kọ̀wọ̀ ní yunifásítì ìlú vienna bẹ́ẹ̀sìni lẹ́yìn ìgbà tó di olóṣèlú ó di agbẹnusọ/olórí ẹgbẹ́ aláwọ̀-ẹwé ilẹ̀ austríà |
hubert minnis hubert alexander minnis on ọjọ́ìbí 16 april 1954 ni olóṣèlú ará ilẹ̀ àwọn bàhámà àti alákóso àgbà ilẹ̀ àwọn bàhámà láti oṣù karùn ọdún 2017 |
coco gauff cori coco gauff ọjọ́ìbí march 13 2004 ni agbá tẹnísì ará amẹ́ríkà òhun ni agbá tẹnísì ọmọ-ọdún kékeré jùlọ tó wà ní top 100 lórí women's tennis association wta bẹ́ẹ̀sìni ipò rẹ̀ tó gajùlọ ni no 49 lágbàayé nínú ìdíje àwọn ẹnìkan àti ipò no 42 nínú ìdíje àwọn ẹni méjì gauff gba ife-ẹ̀yẹ wta ìdíje àwọn ẹnìkan ... |
ìjàmbá ìtúká ẹ̀búté bèírùtù ọdún 2020 ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 2020 àwọn ìjàmbá ìtúká aláriwo olóró méjì ṣẹlẹ̀ ní èbúté ìlú bèírùtù tó jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè lẹ́bánọ́nù ìtúká aláriwo kejì lágbára tó bẹ́ẹ̀ tó ó fa ikú àwọn ènìyàn tó pọ̀ tó 207 ìpalára àwọn ènìyàn tó tó ẹgbẹ̀fàlélẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta ìbàjẹ́ àwọn ohun ... |
àwọn ìbẹ́túká tó ṣẹlẹ̀ ní ẹ̀búté bèírùtù ọdún 2020 |
ajàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní làìbéríà àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé ó tàn dé orílẹ̀-èdè liberia ní àárín oṣù kẹta ọdún 2020 bí ó ṣe bérẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ní... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní rùwándà àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ni wọ́n fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè rùwándà ní oṣù kẹta ọdún 2020 bí àrùn covid-19 ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kini ọdún 2020 àjọ elétò ìlera àgbáyé world health organization jẹ́rìsí i pé kòkòrò àrùn ẹ̀rànkòróná ni ó fa àrùn atẹ́gùn ní àárín ọ̀pọ̀ ènìyàn ní... |
ajàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè liberia |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orilẹ̀-èdè togo |
ilè òlòminira cameroon |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè cameroon |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè zambia |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè gabon |
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 |
ermias joseph asghedom |
nipsey hussle ermias joseph asghedom august 15 1985 march 31 2019 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìtàgẹ́ rẹ̀ bíi nipsey hussle ó sábà kọ ọ́ bíi nipsey hule jẹ́ olórin rap alákitiyan àti oníṣòwò ará amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ wá láti los angeles ní àrin àwọn ọdún 2000 hussle dá fúnrara rẹ̀ gbé àwo-orin mixtape àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde slauson... |
amitabh bhattacharjee amitabh bhattacharjee ọjọ́ìbí 15 august 1973 ni òṣeré ará india tó ún ṣeré nínú àwọn fílmù èdè bengali àti hindi ó dàgbà ní delhi ó kọ́kọ́ ṣeré nínú fílmù rasta tí bratya basu ṣe olùdarí pẹ̀lú mithun chakraborty ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀ fílµu lédè bengali àti hindi |
amitabh bachchan amitabh bachchan orúkọ àbísọ inquilaab srivastava ní 11 october 1942 ni òṣeré olóòtú fílmù atọ́kùn ètò tẹlifísàn akọrin àti olóṣèlú ará índíà ó kọ́kọ́ gbajùmọ̀ nígbà ìbẹrẹ̀ àwọn ọdún 1970 fún àwọn fílmù bíi zanjeer deewaar àti sholay |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní rwanda |
shaikh hassan ahmad zaruq pakata |
kaycee madu kaycee kelechi madu jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí amọ̀fin àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè kánádà òun ni mínísítà aṣẹ̀ṣẹ̀yàn ìpínlẹ̀ alberta ní orílẹ̀-èdè kánádà wọ́n dìbò yàn-án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí ìpínlẹ̀ alberta lọ́dún 2019 láti ṣojú ẹkùn ìdìbò electoral district lọ́gbọ̀n ọjọ́ o... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní cape verde |
impact of the covid-19 pandemic on the food industry |
ipa àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 lórí ilé-iṣẹ́ oúnjẹ àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ti ní ipá lórí ile-iṣẹ ounje kari aye bi awọn ijọba orilẹ-ede ṣe gbe awọn ile-ounjẹ ati awọn ile igbafẹ tì lati lè di ìtànkálẹ̀ kokoro naa jakejado agbaye awọn ero to n wọ ile-ounjẹ lojoojumọ ti dinku jọjọ ti a ba fi we iru akoko yii ni ọdun 2019 tít... |
ipa àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 lórí iṣẹ́ ìròyìn consequences of covid-19 outbreak for media and publishing àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 kọjá ọ̀rọ̀ ẹ̀fẹ̀ ipa tó burú jáì ló ní lórí iṣẹ́ ìròyìn pàápàá jù lọ àwọn àwọn oníṣẹ́ ìròyìn káàkiri gbogbo àgbáyé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé-ìròyìn abẹ́lé ni covid-19 ti ṣe àkóbá fún nípa mímú wọn pàd... |
ipa àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 lórí iṣẹ́ ìròyìn |
seal henry olusegun adeola samuel ọjọ́ìbí 19 february 1963 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ bíi seal ni akọrin àti olùdá-orin ará brítánì àwo orin rẹ̀ ti tà tó 20 millionu àwo orin káàkiri àgbáyé pẹ̀lú orin rẹ̀ crazy tó gbéjáde ní ọdún 1991 àti kiss from a rose tó gbéjáde ní ọdún 1994 |
ajàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní orílẹ̀-èdè ivory coast ongoing covid-19 viral pandemic in cotê d'ivorie àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 wo orílẹ̀-èdè ivory coast ní inú oṣù kẹ́ta ọdún 2020 bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2020 àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn kòrónà tí a tún ń pè ní kofid-19 ní orílẹ̀-m à... |
pápá parsonage ní nuenen pápá parsonage ní nuenen duki tí wọ́n tún máa ń pè ní pápá parsonage ní ìsun-omi nuenen duki tàbí pápá ìsun-omi duki f185 jh484 jẹ́ isẹ́-ọ̀nà àwòrán yíyà ayé àtijó tí wọ́n fi epo yà ní sẹ́ńtúrì ókàndínlógún sẹ́yìn tí oníṣẹ́-ọ̀nà ayawòrán vincent van gogh ṣẹ̀dá lóṣù karùn-ún ọdún 1884 nígbà tí ó... |
ipa ajakaye arun covid-19 lori ona ati asa adayeba ajakaye - arun erankorona odun2019-2020 ni ipa ojijji ati idaran lori awon ona ati eka asa adayeba idaamu ilera kariaye ati aidaniloju abajade lati odo ipa awon ajo bi eni kookan - ti a gba sise ati awon to daduro kaakiri eka naa awon eka ona ati asa adayeba n gbiyanju... |
àwọn ọmọ yorùbá |
ọmọ ẹdó |
gbágùúdá yuca túndarí síbí yìí fún the unrelated-new world plant ẹ wo yucca species of flowering plant in the spurge family euphorbiaceae gbágùúdá jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó máa ń ta nínú ilẹ̀ káàkiri àgbáyé ni àwọn àgbẹ̀ máa ń dáko gbin gbágùúdá ó jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí wọ́n ti máa ń mú oríṣiríṣi oúnjẹ jáde láti ara rẹ̀ |
ajàkálẹ̀ àrùn covid-9 ní orílẹ̀-èdè ivory coast |
oluwaseyi makinde |
bí ayé bá tún dá'adé when life is good again bí ayé bá tún dá'adé when life is good again jẹ́ orin tí arábìnrin akọrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ dolly parton tí ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà kọ wọ́n gbé orin yìí jáde lábẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbórin-jáde butterfly records ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 2020 dolly parton ni ... |
ipa ajakaye arun erankorona 2019-2020 lori idaraya oloko ajakaye arun erankorona ti fa idiwo fun ere idaraya lori oko kaakiri agbaye sise afihan re lori gbogbo awon ere idaraya ni gbogbo agbaye ati si awon iwon lorisirisi isele ati idije ti di fifagile tabi sun siwaju awọn supercars ti ilu ọstrelia ere-idije ti superca... |
ọmọ isoko |
harlem harlem jẹ́ adugbò ni ariwa apakan ti ìlú new york city nínu ìlẹ̀ manhattan o ti ni ihamọ ni aijọju nipasẹ frederick douglass boulevard st nicholas avenue ati morningside park ni iwọ-oorun odò harlem ati opopona 155 ni ariwa fifth avenue ni ila-oorun ati central park north ni guusu agbegbe harlem ti o tobi ju ọpọ... |
ipa àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 lórí eré orí ìtàgé aspect of viral outbreak àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní à bá máa pè ní bàsàjẹ́ nítorí kò sí abala ìgbé ayé tí kò ṣe àkóbá fún láti ìgbà tí ó ti bẹ́ sílẹ̀ láti ọdún 2019 covid-19 ṣe àkóbá lọ́pọ̀pọpọ̀ fún gbogbo abala ère orí ìtàgé nítorí ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ àti títìpa àwọn gbọ... |
bí ayé bá tún dá'adé |
ipa àjàkáyé àrùn erankòrónà 2019-2020 lórí ìdárayá ọlọ̀kọ̀ àjàkáyé àrùn erankòrónà ti fa ìdíwọ fún eré ìdárayá lórí ọkọ káàkiri àgbáyé síse àfihàn rẹ lórí gbogbo àwọn ere ìdárayá ní gbogbo àgbáyé àti sí àwọn ìwọn lórísirísi ìsẹ̀lẹ̀ àti ìdíje ti di fífagilé tàbí sún síwájú awọn supercars ti ilu ọstrelia eré-ìdíje ti sup... |
seyi makinde |
bisola aiyeola bisola omo aiyeola jẹ́ òṣeré filmu ati olorin ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n bí ni oṣu kini ọjọ mokanlelogun ọdun 1986 ní 2017 bisola di oludije akọkọ ti big brother naija ni ọdun 2018 ó gba ẹbun amvca trailblazer ni awọn aṣayan aṣayanyan afirika 2018 ìgbà èwe ile iwe giga national open university of nigeria ... |
àkójọ àwọn oṣere naijiria àwọn wọ̀nyí ni àkójọ àwọn òṣèré ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà |
richard steven horvitz richard steven horvitz july 29 1966 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
ọ̀jọ̀gbọ́n ayọ̀ akínwálé ọ̀jọ̀gbọ́n ayọ̀ akínwálé jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò olùgbéré jáde ati olùkọ́ àgbà fásitì ìgbésí ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí akínwálé ní ìlú ìbàdàn ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ oníwé mẹ́wàá ti methodist high school àti yunifásítì ìlú ìbàdàn ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe t... |
pepsi ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the beverage fún its manufacturer ẹ wo pepsico fún other uses ẹ wo pepsi disambiguation type of soda manufactured by pepsico pepsi jẹ́ ọtí ẹlẹ́rì-dòdò tí ilé-iṣẹ́ pepsico ṣe ọ̀gbẹ́ni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ caleb bradham ni ó kọ́kọ́ ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 1893 tí ó sìn pè é nígbà náà ní brad's drink l... |
andré sogliuzzo andré sogliuzzo august 10 1966 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
bím̀bọ́ ọ̀ṣhìn |
jimoh aliu jímọ̀ àlíù mfr november 11 1939 september 17 2020 tí a tún mọ̀ sí àwòrò jẹ́ agbẹ́gilére òṣèré orí-ìtàgé ati sinimá olùkọ̀tàn àti adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí alàgbà jímọ̀ ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1939 ní ìlú òké-ìmẹ̀sí ní ìpínlẹ̀ èkìtì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà bàbá rẹ̀ àlíù... |
iza isabela cristina correia de lima lima ọjọ́ ìbí ọwẹwẹ 3 1990 tí à mọ̀ nípasẹ̀ orúkọ ìpele rẹ̀ iza jẹ́ akọrin ti ìlú brazil to tún jẹ́ akọrin ati onijo to dide gba òkìkí láti ìkọ́ orin ti àwọn akọrin biì beyoncé rihanna ati sam smith lori ètò youtube ẹ ó tún tí fi àwọn orin rẹ̀ sórí spotify àti soundcloud ní òṣù èbib... |
iza singer |
laycon ọlámilékan moshood agbélẹ̀ṣe tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí laycon ní woọ́n bí lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 19938 november 1993 jẹ́ gbajúmọ̀ olùdíje tí ó borí ìdíje ètò-ìgbafẹ́ ẹ̀rọ tẹlifíṣàn big brother naija ìpele karùn-ún ó jẹ́ olórin-tàkasúfèé àti oǹkọ̀wé orin ọmọ orilẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí-ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ lá... |
laycon ọlámilékan agbélẹ̀ṣe |
chuy bravo jesús melgoza december 7 1956 december 14 2019 je osere ara amẹ́ríkà |
àmójútó ijamba ile-iṣẹ fún covid-19 fidio ti o wa l'ode amojuto ijamba ile ise ni akoko covid-19 jẹ a ko jọ pọ awon ohun elo ti a le fi dẹkun ijamba ni ibi iṣẹ lati le dena ajakalẹ arun covid-19 |
ike barinholtz isaac ike barinholtz february 18 1977 je osere ara amerika |
mc tha mc tha ipele orukọ ti thais dayane da silva são paulo may 7 1993 ni a brazil singer ati silẹ igbesiaye ati iṣẹ bi ati dagba ni idile irẹlẹ ni adugbo ti cidade tiradentes ni igberiko ila-oorun ti são paulo awọn obi rẹ yapa nigbati o wa ni ọmọde ti o ni arakunrin aburo niwon igba ewe o feran lati kọ awọn ewi o dag... |
emmanuel ifeajuna emmanuel arinze ifeajuna tí a bí ní ọjàọ́ kaẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹsàán ọdún 1935 tí ó sì papò da ní ọdún 1967 jẹ́ ọmọ ológun ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti eléré ìdárayá ní ẹ̀ka igi fífò òun ni ọmọ orílẹ̀-èdè adúláwọ̀ àkọ́kọ́ tí ó gba àmì ẹ̀yẹ wúrà níbi ìdíje àgbáayé ní ibi eré ìdárayá ti ìjọba gẹ̀ẹ́sì gbé k... |
rẹ̀mí fàní-káyọ̀dé olóyè victor babárẹ̀mílẹ́kún adétòkunbọ̀ fàní-káyọ̀dé qc tí ó jẹ́ aṣòfin àgbà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà san con ni wọ́n bí ní ọdún 19211995 ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn aṣíwájú àti amòfin àgbà ní orílẹ̀-èdènàìjíríà óntún jẹ́ olóṣèlú bákan náà ọlọ́lá ajìjà-n-gbara àti amòfin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n yàn... |
rẹ̀mí babalọlá adérẹ̀mí w babalọlá jẹ́ mínísítà ìpínlẹ̀ fún ètò ìṣúná ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti 9jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 2007 sí ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàán ọdún 2010 rẹ̀mí jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé-ìfowópamọ́ ó kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísíta ètò ìṣúná látàrí awuyewuye tí ó jẹyọ lórí ọ̀rọ̀ tí ó s9 wípé àwọn k... |
decolonise the internet nigeria/yorùbá wikipedia bí ó ṣe bẹ̀ré àjọ jẹ́ àjọ kan tí ó ń mojú tó àṣà abínibí kan ní orílẹ̀-èdè agbáyé tí ó fìdí kalẹ̀ sí orílẹ̀-èdè germany wọ́n ma ń gbé àṣà àti ìṣe orílẹ̀-èdè germany lárugẹ jákè-jádò àgbáyé tí wọ́n sì ma ń tún ṣe alábàápín àṣà àti ibikíbi tí wọ́n bá ti dé láyé àjọ wikimed... |
ìsàmì ọgọ́ta ọdún òmìnira ilẹ̀ nàìjíríà |
ipa àjàkáyé àrùn erankòrónà 2019-2020 lórí ìdárayá ọlọkọ |
ipa ajakaye arun covid-19 lori ona ati asa adayeba |
ada udechukwu ada udechukwu bii ni odun 1960 je osere ati akewi ni orile ede naijiria itan ibeerepepe aiye re won bi ada si ipinle enugu baba re je omo eya igbo iya re si je omo ile amerika ada dagba ni orile ede naijiria sugbon oun ati awon molebi re lo si ilu amerika nigba ti ogun biafra bere won si pada leyin ti ogu... |
nafisa abdullahi nafisat abdulrahman abdullahi ti gbogbo eniyan mọ si nafisat abdullahi bii ni ojo ketalelogun osu kiini odun 1992 jẹ oṣere adari oluyaworan ati oniṣowo lati ilu jos ni ipinle plateau ni orile ede naijiria nafisat gboye ninu eko ere ori itage lati ile eko giga ti university of jos o ti gba ọpọlọpọ awọn ... |
akinola maja oloye akinola maja md jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà oníṣòwò onínúrere àti olóṣèlú ẹni tí ó jẹ́ ààrẹ fún ẹ̀ka àwọn ọ̀dọ́ ti ilẹ̀ nàìjíríà nigeria youth movement láti ọdún 1944 sí ọdún 1951 lẹ́hìnná àn ni ó wá di ààrẹ fún ẹgbẹ́ ọmọ oduduwa ní ọdún 1953 oloye maja jẹ oyè ti bàbá èkó àti jagunmólú ... |
uzo aduba american actress uzoamaka nwanneka bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1981 tí orúkọ inagi rẹ jẹ uzo aduba je òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú eré orange is the new black tí ó ti kó ipa suzanne ni ọdún 2013-2019 ni ibi tí ó ti gbà ẹ̀bùn outstanding guest actress ni ọdún 2014 àti outstandin... |
tonto dikeh tonto charity dikeh bìì ńì ọ̀jọ́ kẹ́sáń òṣùkèjé ọ̀dùń1985 jẹ́ òlòrìń átì òṣèré òrìlẹ́- édé náìjírìá ńì ọ̀jọ̀ kẹ́tádìlọ̀gbọ̀ń òṣù kẹ́jọ̀ ọ̀dùń 2000 tonto dikeh dá ẹ́gbẹ́ rẹ́ kàlẹ́ èyì tì ò pè ńì the tonto dikeh foundation ẹ́gbẹ́ ńáà wá látì pèsé ìgbè àìyè tò rọ̀rùń fùń àwọ̀ń òbìńrìń ọdọọ̀mọ̀dèbìńrìń átí awọ̀... |
jádesọ́lá òṣíbẹ̀rù jadesola osiberu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó yan iṣẹ́ kíkọ ìtàn sinimá àgbéléwò tí ó sì tún jẹ́ adarí eré orí-ìtàgé àti olùgbéré jáde láàyò ìbẹ́rẹ́ ayé àti ètò ékọ́ rẹ̀ wọ́n bí jádesọlá sí ìdílé ọba tí bàbá rẹ̀ jẹ́ adéwálé òṣíbẹ̀rù ti ìlú ẹ̀pẹ́ ṣàgámù jádesọlá bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kó oníwé mẹ́wàá rẹ̀ ní ìlú... |
billy west william richard billy werstine april 16 1952 je osere ara amerika |
adunni ade adunni ade tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1976 jẹ́ òṣèré àti aláwòṣe ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríàadunni ade je okan gbogi lara awon omo egbe osere amohun maworan ni ere ori itage ti yoruba ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ àti ẹ̀kọ́ a bí adunni ní agbèègbè ti ayaba ìlú niu yoki queens new york ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ìyá rẹ wá l... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.