raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
samuel akínsànyà samuel akínsànyàtí wọ́n bí lọ́jọ́ kìíní oṣù kẹjọ ọdún 1898 tí ó sìn kú lọ́dún 1985 1 august 1898 1985 jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ òṣìṣẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó gbé ní ìlú èkó nígbà ayé àwọn òyìnbó amúnisìn ó jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n pè ní nigerian youth movement bákan náà ó jẹ́ ọba ... |
akinọlá maja |
rahama sadau rahama sadau ti a bi ni ọjọ keje oṣu kejila ọdun 1993 jẹ oṣere ọmọ nàìjíríà ase fiimu ati akorin ilu kaduna ni a bi si ibe na de lo dagba si rahama kopa ninu awọn idije ijó ati ere nigba ti owa ni ọmọde ati lakoko awọn ile-iwe rẹ o dide si okiki ni ipari ọdun 2013 lẹhin ti o darapọ mọ ile- iṣẹ fiimu fiimu ... |
amaka igwe amaka igwe tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù ṣéẹ́rẹ́ ọdún 1963 - ó di olóògbé ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù igbe ọdún 2014 amaka igwe jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà àti ọ̀gá sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ òun ni aláṣẹ iléeṣẹ́ rédíò top 908 èkó àti iléeṣẹ́ amaka igwe studio ipa rẹ̀ lásìkò ìgbédìde fíìmù àgbéléwò láyé sinimá ní nàìjíríà... |
flora shaw dame flora louise shaw tí wọ́n ń dà pè ní flora shaw jẹ́ aya alákòóso ilẹ̀ nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí ìyẹ frederick lugard ní àsìkò tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà wà ní oko ẹrẹ́ àmúnisìn àwọn gẹ̀ẹ́sì wọ́n bi ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejìlá ọdún 1852 ó ṣaláìsí ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù kíní ọdún 1929 19 december 1852 25 janu... |
shan george shan george je olorin osere ati adari ere ni orile ede naijiria ki o to kopa ninu ere thorns of rose o ti kopa ninu ere wind of destiny ni odun 1997 o di gbajumo nipa ipa ti o ko ninu ere outkast ati welcome to nollywood ibeerepepe aiye re won bi shan si ilu abi ni ipinle cross river ni orile ede naijiria m... |
osas ighodaro osas ighodaro bii ni ojo kerindinlogbon osu kewa je osere ati atokun eto ni orile ede naijiria ati amerika o gba ipo omidan alawodudu ni orile ede usa ni odun 2010 o da egbe joyful joy foundation kale lati le doju ija ko aarun iba ni odun 2014 o se atokun eto fun african magic viewers choice awards o ko i... |
efe irele efeilomo michelle irele ni a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsàn án ó jẹ́ òṣèré àti aláwọ̀ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà orúkọ tí gbogbo ènìyàn mọ ọ sí ni efe irele ìbẹ̀rẹ̀ ayè rẹ àti iṣẹ́ rẹ efe irele bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aláwọ̀ṣe rẹ ní ọmọ ọdún márùndínlógún ó ti farahàn nínú oríṣiríṣi ìpolówó ó gba oyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ sociolo... |
nse ikpe-etim nse ikpe-etim tí a bí ní ọdún 1974 jẹ́ òṣèré ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà òkìkí rẹ̀ kàn ní ọdún 2008 fún ipa rẹ̀ nínú reloaded wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ dirama òṣèrébìrin tó dára jù fún ẹ̀dá-ìtàn nse nínú journey to self ní africa viewers awards lọ́dún 2014 ibẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé wọ́n bí etim ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù... |
ini edo ini edo ti a bi ni ọjọ matelogun osu kerin ni odun 1982 jẹ oṣere ọmọ nàìjíríà o bẹrẹ iṣẹ fiimu rẹ ni ọdun 2000 ati pe o ti ṣe ifihan ni diẹ sii ju awọn fiimu ogorun lati igba akọkọ rẹ ni ọdun 2013 o jẹ adajọ fun miss black africa uk pageant ni ọdun 2014 ajo agbaye yan iyaafin edo gẹgẹ bi aṣoju agbaye awọn eto i... |
alain delon alain delon jẹ oṣere ara ilu faranse ti a bi ni oṣu kẹwa ọjọ 8 ọdun 1935 ni sceaux o jẹ ọkan ninu awọn oṣere olokiki ti akoko rẹ ami idanimọ gidi kan ninu awọn 60s o yarayara di irawọ agbaye ti a mọ fun awọn iṣe nla rẹ ni orilẹ-ede yii 135 milionu eniyan ti wo awọn fiimu rẹitọsọna fiimu meji |
omoni oboli omoni oboli ti a bi ni ọjọ kejidilogun osu kẹrin ọdun 1978 jẹ oṣere ara ilu nàìjíríà onkọwe iwe oludari fiimu oludasiṣẹ ati onise fiimu oni-nọmba o kẹkọọ ni ati pe o ti kọ ọpọlọpọ awọn ifihan iboju gege bi the figurine 2009 ' 2010 fatal imagination ' ' ati ' 2016 ni ọdun 2018 o ṣe irawọ ati itọsọna fiimu aw... |
yvonne nelson yvonne nelson ti a bi ni ojo kejila osu kankanla ni odun 1985 jẹ oṣere ara ilu ghana awoṣe o nse fiimu ati iṣowo o ti ṣe irawọ ni ọpọlọpọ awọn fiimu gegebi 2013any other monday in april and swings igbesi aye ibẹrẹ yvonne nelson ni a bi ni accra ghana o jẹ iran ti awọn eniyan fante ati awọn eniyan ga o bẹr... |
jackie appiah jackie appiah ti a bi ni ojo karun osu kejila odun 1983 omo ilu ghana ti a bi si canada fun iṣẹ rẹ gege bi oṣere o ti gba ọpọlọpọ awọn ẹbun ati awọn ifiorukosile pẹlu awọn ẹbun fun oṣere ti o dara julọ ni iwaju aṣoju ni awọn aami- odun 2010 ati oṣere ti o dara julọ ni ipa atilẹyin kan ni awọn ni ọdun 2007... |
kiki omeili nkiruka kiki omeili jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ fún ipa lovette tí ó kó nínú eré lekki wives àwọn ẹ̀yán tún mo fún ipa blessing tí ó kó nínú eré gbomo gbomo express ni ọdún 2015 ìbéèrè pẹpẹ aiyé rẹ àti ẹ̀kọ́ re wọ́n bí omeili sì ìlú èkó ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó sì jẹ ọmọ ìkejì láàrin àwọn ọm... |
ali nuhu ali nuhu mohammed táabì ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta ọdún 1974 jẹ́ òṣèré ará nàìjíríà àti olùdaríó má ń ṣe ère haúsá àti ère gẹ̀ẹ́sì àwọn òní ròyìn má ń pè ní king of kannywood tàbí sarki kannywood ni orúkọ ilé ìṣe fímù hausa nuhu ti kópa nínú àwọn ère nollywood àti kannywood tí ó tó ẹ̀dẹ́gbẹ́ta filmu early life... |
ìbò ìbò ni a lè pè ní ìlànà kan tí ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn gbà fìmọ̀ ṣọ̀kan fọwọ́sowọ́pọ̀ kí wọ́n sì fi ẹnu kò lápapọ̀ láti yan ẹnìkan yálà ọmọdé ni tàbi àgbàlgba sípò kan kí ó lè máa ṣojú wọn ní ipò àṣẹ tàbí ìgbìmọ̀ tí wọ́n torí rẹ̀ yàán nínú ètò ìjọba àwa-arawa oríṣiríṣi ọ̀bà ni a lè gbà dìbò láti yan ẹnikẹ́ni tí a bá f... |
kehinde bankole kehinde bankole jẹ́ òṣèré ará nàìjíríà àwòkọ́ṣe àti olùgbàléjò ó bẹ̀rẹ̀ssí ní kópa nínú ìṣe tíátà nínu eré superstory tí wálé adénúgàó jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ìdílé èyaàn mẹ́fà ó ní ìbejì tí ó má ń kópa nínú eré ní ẹ̀kànkàn ìgbésí ayé rẹ̀ ó jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ìdílé èyaàn mẹ́fà ó ní arábìnrin ìbejì kan tí ó m... |
ali nuhu |
lizzy jay lizzy jay tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ adéyẹlà adégbolá tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tún mọ orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ mìíràn sí ọmọ ìbàdàn jẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín ará nàìjíríà agbanilálejò olórin àti ẹni àwòkọ́ṣe abí lizzy jay ní ọjọ́ 18 oṣù kẹ̀sán 1995 ní ìlé ifẹ̀ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun bàbá rẹ̀ jẹ́ olóṣèlú tí màmá rè sí jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọbaó lọ i... |
nadia buari nadia buari ti a bi ni ojo kankanlelogun osu kankanla odun 1982 je osere ilu ghana o gba awọn yiyan meji fun osere to dara julo ni ni odun igbesi aye ibẹrẹ buari ni a bi ni sekondi-takoradi ghana baba re wa lati lebanoni iya re si wa lati ilu ghana o lọ si ile-iwe secondary ti awọn ọmọbinrin mfantsiman ati ... |
pierra makena pierra makena ti a bi ni ojo kankanla oṣu kẹrin ọdun 1981 jẹ jockey disiki ti ara ilu kenya oṣere ati eniyan tv o gba ami eye oṣere ti o ni atilẹyin ti o dara julọ fun ipa rẹ ni when love comes around ni ajọdun nollywood ati afirika fiimu awọn afirika ni ilu los angeles awọn ọdun ibẹrẹ ati ẹkọ makena ni a... |
toni tones gbemi anthonia adefuye ti oruko inagi re je toni tones je osere agohunsafefe ati ayaworan ni orile ede naijiria won bii ni osu keje o si je abikeyin ninu awon omo marun ti awon obi re bi o lo si ile eko queen's college o gboye ninu eko itaja ati isiro ni ile eko giga ti university of lancaster ni orile ede u... |
jeillo edwards jeillo edwards ti a bi ni ojo ketalelogun oṣu kẹsan odun 1942 freetown sierra leone - o se alaisi ni ojo keji osu keje 2004 london england jẹ oṣere ara ilu sierra leone ẹniti a mo dada ninu itan awọn oṣere dudu ni ilu gẹẹsi o jẹ obinrin akọkọ ti idile afirika lati kẹkọọ ere-idaraya ni london's guildhall ... |
eniola badmus eniola badmus tí a bí ní oṣù kẹ̀sán ọjọ́keje ọdún 1983 òṣèré fíìmù ti ilu nàìjíríà arábìnrin náà bẹ́ẹ̀ sí ní òkìkí ní ọdún 2008 lẹ́hìn tí o ṣe ìfihàn nínu fiimu jenifa eniola jẹ́eẹni bíbí ìlú èkó ní nàìjíríà ó ní ẹkọ ìpìlẹ̀ àti ilé-ìwé gíga ní ìjẹ̀bú òdeó lọ sí yunifásítì ti ìbàdàn ní biti ó ti kẹ́kọ̀ọ́ t... |
ashley callie ashley callie ojo ogbon oṣu kejila ọdun 1976 - ojo karun din logun osu keji odun 2008 jẹ oṣere ara ilu south africa ti a mọ julọ fun ipa rẹ gege bi leone haines ni isidingo 2000-08 o ku ni ọjọ karundinlogun oṣu kẹji ọdun 2008 nitori abajade awọn ipalara ori lati ikọlu ọkọ ayọkẹlẹ ni johannesburg south afr... |
chika ike chika 'nancy' ike ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1985 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré jáde olókòwò ẹlẹ́yinjú àánú 9mọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí chika ní ìlú onitshaní ìpínlẹanambrateó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣeré ìtàgé ní inú ilé-ìjọsìn nígbà tí ó wà ní dédé ọmọ ọdún mẹ́fà ó tẹ̀ siwájú láti ma ṣ... |
dwight david eisenhower |
chester alan arthur |
james abram garfield |
thishiwe ziqubu thishiwe ziqubu ti a bi ni ojo karun osu kejo odun 1985 je ako ere oludari ere ati osere ti owa lati ilu south africa won gba ami eye best actress in a supporting role ni fun ipa won gege bi tashaka ninu ere ife ' ni odun 2019 won shey oludari awon ipele kankan ninu ' eko ziqubu keko nipa kiko ere ati p... |
bimbo oshin bimbo oshin jẹ́ òní fíìmù ti orílè-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti iṣẹ́ a bí ni oṣù kẹrin ọjọ́ 24 ọdún 1971 ni ìpínlè òndó ìlú kan ní gúúsù ìwọ-oòrùn nàìjíríà ó lọ sí yunifásítì ti èkó ní bití ó ti gba oyè bachelor of arts ba ni philosophy bimbo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1996 ṣùgbọ́n dìde sí ìdánimọ... |
ilfenesh hadera ilfenesh hadera ti a bi ni ojo kini osu kankanla odun 1985 je osere o ko pa ninu fiimu ti oj jade ni odun 2017 gege bi ni ojo kankandilogbon osu kesan hadera bera si ni kopa mayme johnson iyawo ni ifi lole jara titi american lori igbesi aye ibẹrẹ a bi hadera ni ojo kini osu kankanla ni ilu harlem oje om... |
ruth negga ruth negga tí a bí ní ọ́jọ́ keje oṣù kíní ọdún 1982 jẹ́ osere ethiopian-irish ti a mo fun ipa re ni jara telifisonu amc ' ati ninu fiimu ' negga ti kopa ninu awon fiimu bi capital letters 2004 ti a mo si trafficked ni awon orilede mi ' 2005 ' 2005 ati 2016 awon ise imi toti ko pa ninu re je ' ' ' and 's ' ne... |
joy fm ghana ayo fm jẹ ibudo redio ti aladani ni akráolu-ilu ghaná ile-iṣẹ ibudo naa jẹ ohun-ini ati ṣiṣe nipasẹ ile-iṣẹ ẹgbẹ ẹgbẹ media multimedia group limited o ṣee ṣe ariyanjiyan ibudo redio ti o jẹ olori ni ghana ti o ṣe igbasilẹ ni ede gẹẹsi |
bimbo ademoye bimbo ademoye jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà ní ọdún 2018 a yán fún òṣèré tí ó dára jùlọ nínú eré ìpanilẹ́rìn-ín / tv jara ní ọ̀dọ̀ àwọn àṣàyàn áfíríkà fún ipa rè nínu fíìmù backup wife 2017 ó tún ńṣe ìràwọ̀ rok tv ìkànnì 329 ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹkọ rẹ̀ a bí ademoye ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin ọdún 1991 ní lagos g... |
house of gold house of goldtí a gbé kalè gẹ́gẹ́ bí family runs lórí dvd eré àwàdà tí ghana ati nàìjíríà tí olùgbékalẹ̀ rẹ̀ jẹ́ yvonne nelson àti oludari rè jẹ́ pascal amanfo àwọn ìràwọ̀ bíi majid michel yvonne nelson omawumi megbele mercy chinwo ice prince zamani eddie watson àti francis odega kò pa nínú rẹ̀ fíìmù náà ... |
carl reiner carl reiner march 20 1922 june 29 2020 je osere ara amerika |
ghada abdel razek ghada mohammed abdel razek ede larubawa غادة محمد عبد الرازق abi ni ojo kefa osu keje odun 1970 oje osere ilu egypt o bere ise re gegebi osere ni odun 1997 oti kopa ninu orisirisi ere osi ti gba ami eye pupo igbesi aye ibẹrẹ won bi abdel razek si kafr saqr sharqia governorate ni odun 1970 ohun lo ker... |
asmaa abulyazeid asma abulyazeid èdè lárúbáwá أسماء أبو اليزيد jẹ́ akorin àti òṣèré tí ó wá á laìlúiu egypt ó kẹ́kọ̀ọ́ ìtanràn àwòrán ode kó pa nínú eré orí ìtàgé ní tíátà hanager ó sì díje fún àmì ẹ̀yẹ sheikh sultan al qasimi fún eré ìtàgé tí ó dára jùlọ ní ọdún 2016 ó fa àkíyèsí sí ara rẹ̀ nítorí ipa tí ó kó nínú ja... |
tamara eteimo tamara eteimo bíi ni ọjọ́ kerìnlélógún oṣù keje ọdún 1987 tí orúkọ inagi rẹ jẹ tamara jones je òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó kọ́kọ́ farahàn ni nollywood ni ọdún 2011 ó gbé ipò kejì láàrin àwọn òṣèré bìnrin ni nollywood ni ọdún 2013 ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of port harcourt níbi tí ... |
louise barnes louis barnes bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1974 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó di gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré surviving evil ni ọdún 2009 ó kọ ipa miranda barlow nínú eré black sails ni ọdún 2014 ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí barnes sì ìlú kwaszulu-natal ó sì gboyè nínú ìmò dramati... |
mary twala mary kuksie twala bíi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1939 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ní ọdún 2011 wan yàn kalẹ̀ fún ẹ̀bùn best actress in a supporting role lati ọdọ africa movie academy award iṣẹ́ twala tí kópa nínú orísìírísìí eré ìbílẹ̀ ni south áfríkà ó kópa nínú eré hopeville gẹ́gẹ́ bíi ma d... |
pearl thusi sithembile xola pearl thusi bíi ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 1989 jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni south áfríkà thusi ni òkìkí fún ipá patricia kopong tí ó kó ni ère the no 1 ladies' detective agency ó kọ ipa dayana mampasi nínú eré quantico àti samkelo nínú eré ìfẹ́ catching feelings iṣẹ́ thusi ṣe atọk... |
mary uranta mary data uranta jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà wọn bíi sí ìlú portharcourt ibè sì ni ó gbé dàgbà ó wá lára àwọn tó díje fún ipò obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni ilẹ̀ niger delta ó sì gbé ipò kejì uranta bẹ̀rẹ̀ ère ṣíṣe ni ọdún 2000 pelu eré girls hostel ní ọdún 2006 ó di gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú... |
hadiza aliyu hadiza aliyu bíi ni ọjọ́ kìíní oṣù kẹfà ọdún 1989 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ aṣojú fún ilé iṣẹ́ mtn nigeria àti indomie noodles ó gbà ẹ̀bùn òṣèré tó dára jù lọ ní ọdún 2013 láti ọ̀dọ̀ nollywood awards ó sì gba ẹ̀bùn láti ọ̀dọ̀ kannywood àti mtn ni ọdún 2014 ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ aiyé rẹ̀ wọ́n bí sì ìl... |
estelle reiner estelle lebost june 5 1914 october 25 2008 je osere ara amerika |
mir koks/bimbo ademoye |
àyọ fm ghana |
véro tshanda beya mputu véronique tshanda beya mputu je osere ti o wa lati ilu congo ogba ami eye africa movie academy award fun osere iwaju ti o dara julo fun ipa re ninu igbesi aye ibẹrẹ a bi mputu osi dagba si ilu kinshasa eyi ti o je olu ilu orílẹ̀-èdè olómìnira òṣèlú ilẹ̀ kóngò ise ni odun 2017 o ko pa ninu ni a s... |
khabonina qubeka khabonina qubekabíi ni ọjọ́ kẹji lélógún ọdún 1981 jẹ́ òṣèré agbóhùnsáfẹ́fẹ́ oníjó àti olórin ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ní ọdún 2017 ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ níbi ayẹyẹ boston international film festival awards wọn si yàán kalẹ̀ fún ẹ̀bùn òṣèré bìnrin tó dára jù lọ níbi ayẹy... |
dolly rathebe dolly rathebe bíi ni ọjọ́ kẹji oṣù kẹrin ọdún 1928 jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó kú ní ọjọ́ kerìndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2004 iṣẹ́ ní ọdún 1984 nígbà tí ó kọrin ní bi tí àwọn èèyàn ti ń ṣe fàájì ni ilu johannesburg ní àwọn kan lọ bá wípé kí ó wà ṣiṣẹ́ lọdọ wọn kò pé díè tí ó wà lọ́d... |
jo-anne reyneke jo-anne reyneke bíi ni ọjọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 1988 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá pearl tí ó kó nínú eré muvhando àti prudence oliphant nínú rythm city ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bíi sì ìlú vereeniging ni ilẹ̀ guateng ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ russell high school níbẹ̀ sì ni ó ti n... |
rachel mwanza rachel mwanza je osere ti o wa lati orílẹ̀-èdè olómìnira òṣèlú ilẹ̀ kóngò a mo ju lo fun ipa re komona ninu fiimu rebelle ti o jade ni odun 2012 ki o to ri ipano ko ko ni ile adugbo kinshasa ni o man sun igbesi aye ibẹrẹ odun 1997 ni abi mwanza ni oje omo eketa ninu omo mefa ti awon obi e bi ni oti ilu ig... |
shaleen surtie-richards shaleen surtie-richards bíi ni ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 1955 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré fiela se kind ni ọdún 1988 àti egoli place of gold ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bíi shaleen sí ìlú upingtong ni orílẹ̀ èdè south áfríkà bàbá rẹ̀ jẹ́ olùdarí ilé... |
nana gichuru ephex kanana gichuru ti abi ni ojo kerinla osu kejila odun 1986je osere ati olugbalejo ori telifiosnu omo ilu kenya awon eyan tun mo si nana gichuru gege bii osere pje gbajumo fun awon ipa re ninu awon jara telifisionu ' demigods ati' gegebi olugbalejo ori afefe oye ki ogbe eto interior designs jade ki oto... |
patricia kihoro patricia wangechi kihoro ti a bini ojo kerin osu kini odun 1986 je osere olorin ati adari eto radio ti owa lati ilu kenya o di olokiki nitori pe o kopa ni ipele eketa titi 'eleyi ti o de igbeyin idije na ni pa sise ere akoko ere ti o kopa ninu re je ere miss nobody eleyi je ki o gba yiyan ninu ami eye a... |
nana kagga nana hill kagga macpherson ti atun mo si 'nana kagga-hill tabi 'nana hill' je omo orile ede ùgándà oje osere ako ere onimo ero ati agboroso iwuri o je gbajumo fun ise e ninu gegbi ako ere ati agbe ere jade pataki ati gege bi osere ninu oje okan ninu awon adajo miss uganda ni odun 2018 a bi kagga si ilu nairo... |
flavia tumusiime flavia tumusiime flavia je osere ati agbalejo ori redio ati tefisonu ti owa lati ilu ùgándàemcee ati onkowe o man se eto ni oganjo owuro lori ikani redio ni o ti seto tele ri ni morning @ ntv lori ibiyi na ni o tin se eto gegebi vj fun o ko ipa ninu jara ti se ti akori re je lati odun 2014 titi di odun... |
ile agba ile ifẹhinti lẹnu iṣẹ tabi ile ifẹhinti lẹnu iṣẹ - nigbakan ti a pe ni ile ntọju tabi ile ifẹhinti kan - botilẹjẹpe ọrọ yii tun le tọka si ile ntọju kan - jẹ ile-gbigbe ibugbe pupọ ti a pinnu fun awọn eniyan agbalagba nigbagbogbo gbogbo eniyan tabi tọkọtaya ni ile ni yara kan ti o jọra si iyẹwu tabi iyẹwu ti a... |
fatiha berber fatiha berber odun 1945 titidi odun 2015 je esere omo ilu àlgéríà ti atun mosi fatiha blal igbesiaye a bi fatiha berber ni a won molebi re wa lati ni titi apa ariwa ilu algeria ni odun 1950 okorin pelu awon lehin igba na olo ko eko drama ni conservatory of algiers oludari mustapha gribi fun ni ipa e akoko... |
malika belbey malika belbey ti abi ni ojo kedogun osu kefa odun 1974 je osere ti o wa lati ilu àlgéríà igbesiaye ilu ni won bi belbey si ni apa iwo oorun titi algeriao lo si algiers school of dramatic arts belbey bere ise osere pelu ere ori itage ti akori re je nedjma ti won mu lati iwe ti ko ti ziani cherif ayad se ol... |
tóyìn adégbọlá tóyìn adégbọlá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí aṣẹ́wó tó re mẹ́kà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1961 ó jẹ́ òṣèré sinimá yorùbá olùgbéré-jáde àti adarí eré ọmọorílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá ó bẹ̀ré eré orí-ìtàgé yorùbá ní ọdún 1984 ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣ... |
fisáyọ̀ ajíṣọlá fisáyọ̀ ajíṣọlá tí gbogbo ènìyàn tún mọ̀ sí freezonjẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ṣeré ìtàgé model àti akọrin ó di ìlú mọ̀ọ́ká látàrí ipa tí ó kó nínú eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ jenifa's diary pẹ́lú fúnkẹ́ akíndélé ó tún ma ń kópa nínú eré ọ́lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ this life nectar shadows burning spear circle of interest ... |
sandra prinsloo sandra prinsloo bíi ni ọjọ́ kẹẹ̀dúgún oṣù kẹsàn-án ọdún 1947 tí àwọn èèyàn tún má ń pè ní sandra prinzlow je òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó gbajúmọ̀ fún ipá kate thompson tí ó kó nínú eré the gods must be crazy ni ọdún 1980 ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ re prinsloo sọ wí pé òun kò lérò pé òun má jẹ́ ... |
nthati moshesh nthathi mosheshbíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1969 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà wọn yàn kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ africa movie academy award for best actress in a supporting role ni ọdún 2016 iṣẹ́ nthathi tí kópa nínú àwọn eré bíi soldier soldier home affairs àti human cargo ní ọdún 2014 ó dar... |
florence masebe florence masebe bíi ni ọjọ́ kerìnlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1972 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré muvhango ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù láti ọ̀dọ̀ africa movie award nibi ayeye kẹsàn-án tí african movie academy awards |
nomzamo mbatha nomzamo nxumalo mbatha bíi ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1990 jẹ́ òṣèré agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ọlọ́jà àti ajìjàgbara ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bíi ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1990 sì ìlú kwamashu ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí rippon primary school ni durban àti bechet high school ní ọdún 201... |
thuso mbedu thuso mbendu bíi ni ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1991 jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè south áfríkà wọn yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ emmy awards fún ipá tí ó kó nínú eré is'thunzi ó kọ ipa kitso medupe nínú eré scandal nosisa nínú eré isibaya àti boni khumalo nínú eré saints and sinners wọ́n bíi thuso sì ìlú pelham ni ilẹ̀ kwas... |
bonnie mbuli bonnie mbuli bíi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1979 jẹ́ òṣèré agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati ọlọ́jà ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó ṣe atọkun fun ètò afternoon express ní ọdún 2020 ó kó ipa jasmine hadley nínú eré nought and crosses tí bbc gbé jáde ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí sì ìlú soweto ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ni ... |
sophie ndaba sophie lichaba bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1973 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ẹ̀kọ́ ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ni zimbabwe ìyá rẹ gbé lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn aláìní ìyá kí ó ba le ni ẹ̀kọ́ gidi bàbá rẹ̀ kú ní ọdún 2016 ó bí ọmọ méjì fún ọkọ rẹ tẹ́lẹ̀ themba ndaba ní ọdún 2018 àwọn kan gbé aruyewuye já... |
jessica nkosi jessica ayanda nkosi bíi ni ọjọ́ ogún oṣù kìíní ọdún 1990 jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé re wọ́n bí jessica sì ìlú empangeni ní ìgbà tí ó pè ọmọ ọdún mọ́kànlá bàbà rẹ di aláìsí ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of kwaszulu-natal ó sì gboyè nínú eré ṣíṣe ni ọ... |
dámilọ́lá adégbìtẹ́ nigerian actress dámilọ́lá adégbìtẹ́ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùún ọdún 1985 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti model ó kópa gẹ́gẹ́ bí 'thelema duke nínú eré onígbà-dégbà ti tinsel àti gẹ́gẹ́ bí emi williams nínú eré flower girl ó gba amì-ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tí ó pe... |
túndé aládéṣe túndé aládéṣe jẹ́ olùkọ̀tàn tí ó sì tún ti gba àmì-ẹ̀yẹ ti africa movie academy award for best actress in a leading role ní ọdún 2018ó ti kọ ìtàn ti a 70 night drama fún mtv shuga filmed by the actors themselves over four countries explaining and set during the coronavirus lockdown iṣẹ́ rẹ̀ aládéṣe ti níf... |
neveen dominic neveen dominic je osere agbere jade onisowo ati oninurere ti o wa lati gúúsù sudan ti on gbe ni ilu kánádà igbesi aye ara ẹni ilu south sudan ni wwon bi dominic si oni oselu ni baba e iya e si je osereni igba ti o wa ni omo odun medogun ohun ati awon molebi re ko lo si ilu calgari kanada nigba ti ogun wa... |
mary lazarus màríà lásárù tí a bí ní ọjọ́ karùn ún oṣù karùn ún ọdún 1989 jẹ́ òṣèré àti ò ǹṣe fiimu ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ó gba àmì ẹ̀yẹe lórí fiimu àwọn ènìyàn ìlú fún òṣèré tí ó ní ìlérí tí ó dára jùlọ ní ibi ẹ̀buǹ eré ìdárayá ti i àwọn ènìyàn ìlú city people entertainment awards ti odun 2018 wọ́n sì tún yàn... |
pamela nomvete pamela nomvete bíi ni ọdún 1963 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà wọ́n bí pamela sì orílẹ̀ èdè ethiopia ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ jẹ ọmọ orílẹ̀ èdè south áfríkà ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí royal welsh college of music and drama ní ọdún 1990 nomvete bẹ̀rẹ̀ eré orí tẹlẹfísọ̀nù ó sì di gbajúmọ̀ nípa eré generati... |
halima abubakar nigerian actress halima abubakar ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹfà ọdún 1985 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2011 ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti afro hollywood best actress award ìgbé ayé rẹ̀ wọ́n bí abubakar ní ìpínlẹ̀ kánò àmọ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ kogí ni ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bérẹ̀ ní ìpínlẹ̀ k... |
simoné nortmann simoné pretorius bíi ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1990 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá irma humpel tí ó kó nínú eré vir die voëls ó tún gbajúmọ̀ fún ipá jony tí ó kó nínú eré hotel èyí sì jẹ ki o gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ south afri... |
terry pheto moitgeri pheto bíi ni ọjọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1981 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó gbajúmọ̀ fún ipá miriam tí ó kó nínú eré tsotsi iṣẹ́ lẹ́yìn farahàn nínú ere tsotsi pheto tí kópa nínú orísìírísìí eré míràn bíi catch a fire2006 goodbye bafana 2007 àti how tó steal 2 million 2012 ni oṣù keje ọ... |
nandi nyembe nandi nyembe bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1950 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré zone 14 àti soul city ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ayé re wọ́n bíi nyembe sì ìlú kliptown ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ni ọdún 1950 ó sì ti gbé ní àwọn ìlú bíi botswana east london àti south ... |
mike bamiloye nigerian film actor evangelistdrama producer and director mike ayọ̀bámi bámilóyè ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹ́rin ọdún 1960 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé adarí eré olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ajíyìn-rere tí ó ma ń lo eré oníṣẹ́ láti fi jèrè ọkàn àwọn ènìyàn ó sì tún jẹ́ olùdásílẹ̀ àti ààrẹ mount... |
ada ameh ada ameh jẹ́ òṣèré ará ìlú nàìjíríà kan tí ó ti lò ju ọdún ogún lọ ní ilé-iṣẹ fíìmù ti nàìjíríà àti pé ó ṣe àkíyèsí jùlọ fún ipa rẹ̀ bi anita ni fiimu 1996 tí àkọlé rẹ̀jẹ́ “ domitilla” àti bi emu johnson nínú eré aláàmì-ẹ̀ye ti àkọlé rẹ jẹ́ johnsons ameh nínu the johnsons ṣe ìfihàn lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn òṣèré nollywo... |
zineb triki zineb triki lárúbáwá ti a bi ni odun 1980 je osere ede french ti owa lati ilu morocco o je olokiki fun ipa re ninu jara èdè faransé titi nadia el mansour ti akole re je the bureau won bi zineb triki ni odun 1980 ni ilu morocco o lo si ile eko elede faranse ni bi ti oti ko imo ere ori itage ati ijo ni igba... |
amal ayouch amal ayouch tí a bí ní ọdún 1966 jẹ́ òṣèré ìlú morocco àti ọdún 1990 ni ó tín ṣe eré lórí ìtàgé àti nínú fíìmù pẹ̀lú èdè faransé ní oṣù kìíní ọdún 2015 wọ́n fún ni àmì ẹ̀yẹ àpónlé ní àyàjò àwọn obìnrin òṣèré tí ó wà yẹ ní brazzaville ayouch ti kópa iwájú nínú morocco's fondation des arts vivants ìpìlẹ̀ àwọn... |
francis odega francis odega jẹ́ òṣèré ẹlẹ́fẹ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ma ń ṣe àwàdà tí ó sì ti gba amì-ẹ̀yẹ fún àwàdà lórí fọ́rán fidio rẹ̀ tí ó gbòde kan lórí ẹ̀rọ ayélujára fọ́nrán fídíò yí ni ó sọ ọ́ si gbajú-gbajà tí ó fi rí ìbáṣepọ̀ òun pẹ̀lú àwọn ìlú mọọ́ká ní òkè òkun bíi 50 cents etò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀ fra... |
deolinda kinzimba deolinda inês caetano kinzimba ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu karun odun1995 jẹ ọmọ ilu angola ti o je akọrin ati oṣere igbesiaye ilu luanda ni won bi kinzimba si sugbon odagba ni ingombota o so wipe ohun lo igba omode ti odun ati pe ati kekere ni toi feran orin awon ti oman wo awokose won ni phyllis hym... |
gbenró ajíbádé gbénró àjíbádé ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kejìlá jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré-jáde model àti olóòtú ètò ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ makurdi international school àti mount saint gabriels secondary school ó jáde ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti benue state university nínú ẹ̀kọ́ biology ó kópa gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ì... |
heloísa jorge heloísa jorge ti won bi ni ojo kini osu keje odun 1984 je osere ati oludari ere ti o wa lati ilu àngólà igbesiaye won bi si chitato ni lunda norte province baba re je omo orile ede brasil iya re si wa lati ilu angola ojuwe ara e gege bi eyan kan ti oju man ti ni igba ti owa ni omodeni igba ti o wa ni omo ... |
lucrécia paco lucrécia paco ti a bi ni ojo kankandilogun osu kewa odun 1969 je osere ti o wa lati ilu mozambique o je okan larin awon osere ti oniyi ju ni mozambique igbesiaye paco dagba ni maputo ni igba ti owa ni omode o feran ki oma ko orin ati ki o ma jo si awon orin ibile eleyi ti ko po nita ki mozambique to gba o... |
yvonne okoro chinyere yvonne okoro je osere omo nàìjíríà ati ghánà baba e wa lati naijiria iya e si wa lati ghana okoro je omo oniran pupo nitori eyi ni ofin man pe ara re ni omo áfríkà yvonne okoro wa lati amankalu alayi ni ìpínlẹ̀ ábíá ilu naijiria o gba ami eye osere ti o dara ju lo ni odun 2010 ni ghana movies awar... |
logun ede logun ede je ti pantheon yoruba gege bi okan ninu awon orishas kekere ninu esin yoruba orisha ọmọ oshún ati oshosi pẹlu awọn abuda hermaphrodite ṣe akiyesi pe oṣu mẹfa ti ọdun jẹ abo ati oṣu mẹfa ti ọdun jẹ akọ nigbati o ba han ni ipo ọkunrin rẹ o n gbe inu awọn igbo bi baba rẹ nigbati o ba ni awọn abuda abo ... |
syndy emade syndy emade ti a bi gege bi elone synthia emade ni ojo kankanlelogun osu kankanla odun 1993 je osere awose ati agbe ere jade omo ilu cameroon oje asoju burandi fun instavoice celeb ohun ni oda ile ise blue rain entertainment awon ere ti oti gbe jade je a man for the weekend and rose on the grave o jade ninu... |
lucie memba lucie memba bos je osere ati aberejade omo ilu cameroon ti won bi ni odun 1987 oti kopa ninu awon ere ede faranse ati ede geesi won ye si pelu ami eye osere iwaju ti o dara ju ni cinema titi cameroon fun awon esere elede faranse ni cameroon movies merit award cmma titi odun 2013 o ko ipa ninu ere nollywood ... |
adrienne koutouan adrienne ako anomgbo koutouan ti a bi ni ọdun 1969 jẹ apanilerin ati oṣere ti o wa lati ilu côte d'ivoire igbesiaye koutouan je omo egbe awon eyan tchaman osi wa lati abule abobo-té ni ilu abobo ti osun mo abidjan ati omode ni oti fe je osere awon obi re o fi gbogbo ara gba ise yi o bere ise gegebi os... |
werewere liking werewere liking ti a bi ni odun 1950 ni ilu cameroon je onkowe ati osere ti on gbe ni abidjan cote d’ivoire o da egbe ori itage ki-yi mbock kale ni odun 1980 osi da abule ki-yi kale ni odun 1985 fun eko imo aworan fun awon odo iwe e elle sera de jaspe et de corail je iwe orin ti o soro nipa misovire nip... |
yemi ajibade yẹmí ajíbádé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù keje ọdún 1929 24 january 2013 ẹni tí wọ́n mọ̀ sí yẹmí ajíbádé yẹmí goodman ajíbádé tàbí adéyẹmí ajíbádé jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé adarí-eré ati olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè england láti ọdún 1950 ó ti kó ipa ribiribi nínú eré orí-ìtà... |
richard mofe damijo nigerian politician and actor richard èyímofẹ́ evans mofẹ́-damijo ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù keje ọdún 1961 ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí rmd jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá olùkọ̀tàn agbẹjọ́rò olùgbéré-jáde àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti fìgbà kan tẹ́lẹ̀ jẹ́ kọmíṣọ́nà fún àti àti ìgbafẹ́ fún ìp... |
fòpin sí sars fòpin sí sars tí gbajúmọ̀ ògbufọ̀ rẹ̀ lédè gẹ̀ẹ́sì túmọ̀ sí end sars jẹ́ ìfẹ̀hónúhàn àwọn ọ̀dọ́ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó bẹ̀rẹ̀ lórí ìtàkùn ayélujáratwitter láti pe ìjọba àpapọ̀ sí fífòpin sí àkànṣe ẹ̀ka ọlọ́pàá agbóguntolè special anti-robbery squad tí wọ́n fẹ̀tẹ̀ sílẹ̀ tí wọ́n wá ń pa làpálàpá nípa híha... |
sola fosudo film actor and scholar ṣọlá fosudo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta ọdún 1958 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé òun sinimá ọ̀mọ̀wéaláríwòye àti adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí ṣọlá ní ìpínlẹ̀ èkó ó kàwé gboyè nínú ìmọ eré oníṣẹ́ láti ilé-ẹ̀kọ ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ university àti un... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.