raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
bọ́lá ọdẹlékè nigerian pastor bọ́lá ọdẹlékè tí wọ́n bí lọ́dún 1850 jẹ́ òjíṣẹ́ ọlọ́run ajíyìnrere nàìjíríà àti bíṣọ́ọ̀bù obìnrin àkọ́kọ́ ní áfíríkà òun ni olùdásílẹ̀ ìjọ power pentecostal church ìgbà èwe rẹ̀ ọdẹlékè jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti ipele kejì ní iléṣà n... |
sandra duru-eluobi sandra chidinma duru-eluobi jẹ́ oníṣòwò àti olùdásílẹ̀ pre-adult affairs organizationòun ni alákoso ilé iṣẹ́ sanchhy nigeria limited zest media and entertainment àti executives cable and electronics company ó jẹ́ onímòràn fún standard organization police women units police service commission àti kulf... |
sarah ladipo manyika sarah ladipo manyika bíi ni ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1968 jẹ́ onkọ̀we ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni olùkọ̀wé in dependence 2009 àti like a mule bringing ice cream to the sun 2016 òun ní olóòtú fún ilé iṣẹ́ ozy ìwé manyika farahàn nínú ìtàn àkọlé àwọn ọmọbìnrin títún ní ilẹ̀ áfríkà ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé... |
saudatu mahdi saudatu mahdi bíi ni ọjọ́ ogún oṣù kẹrin ọdún 1957 jẹ́ àjàfẹ̀tọ́ fún àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ní akọ̀wé fún ẹgbẹ́ women's rights advancement and protection alternative warpa ó ti kọ ìwé tí ó lé ní ogún lórí bí ìyà ṣe ń jẹ àwọn obìnrin mahdi ni ó jẹ́ adarí fún àwọn tó parapọ̀ láti jà fún obì... |
salamatu hussaini suleiman salamatu hussaini suleiman jẹ́ agbejọ́rọ̀ tí ó sì jẹ komísọ́nà lórí ọ̀rọ̀ òṣèlú àlàáfíà àti àbò fún ẹgbẹ́ ecowas ní oṣù kejìlá ọdún 2008 wọ́n fi jẹ mínísítà lórí ọ̀rọ̀ obìnrin àti ìdàgbàsókè ìlú ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí salamatu hussaini suleiman sí ìlú argungun ní ìpínlẹ̀ keb... |
ebun oyagbola adenike ebunoluwa oyagbola bíi ni ọjọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 1931 jẹ́ olóṣèlú tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà bìnrin àkọ́kọ́ ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó sì gboyè náà ní ọdún 1979 oyagbọla jẹ́ ọmọ ilẹ̀ igan aládé ní ìlú yewa north ní ìpínlẹ̀ ogun ó si ṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ ní àwọn ilé ìkẹ́kọ̀ọ́ ní ìlú ye... |
amina mama amina mama tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣú kẹsàn-án ọdún1958 jẹ́ oǹkòwé ajàfúnẹ̀tọ́ àwọn obìnrin àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè gẹẹsi àwọn ǹ kan tí ó dojúkọ gangan ni àwọn ǹ kan tí ó jẹ mọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ lẹ́yìn ìjọba amúnisìn ti ológun àti ti abo amina ti gbé ní orílẹ̀-èdè áfíríkà yúróoṕù àti... |
kehinde olorunyomi kehinde olorunyomi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kíní ọdún 1981 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ònkọ̀tàn àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ eré ṣiṣẹ́ kẹ́hìndé bẹ̀rẹ̀ eré tíátà ní orí eré ọlọ́sọ̀sẹ̀ ti everyday people ọdún 2001 she is remembered for her role in the defunct soap opera domino níbi t... |
abímbọ́lá fashola abímbọ́lá fáṣhọlá abímbọ́lá fáṣhọlá ọjọ́ ìbí 6 april 1965 ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní tẹ́lẹ̀ àti ìyàwó gómìnà àná fún ìpínlẹ̀ èkó babatunde fáṣhọlá abímbọ́lá fáṣhọlá orúkọ abímbọ́lá emmanuela fáṣhọlá ọjọ́ ìbí april 1965 ìbàdàn ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjírià orílẹ̀ èdè nàìjírià ọmọ ìlú nàìjírià iṣẹ́ politicianad... |
ayisat yusuf nigerian footballer ayisat yusuf-arómirẹ́ tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1985 6 march 1985 agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ọmọ nàìjíríà nígbà kan rí orílẹ̀-èdè finland ni ó ń gbé báyìí yusuf ti gbá bọ́ọ̀lù fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ní nàìjíríà àti finland ó wà lára ìkọ̀ agbábọ́ọ̀l... |
mercy macjoe mercy ima macjoe tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí mercy macjoe tí wọ́n bí lógúnjọ́ oṣù kẹfà ọdún 1993 june 20 1993 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin olóòtú sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká fún ipa tó kó nínú sinimá jenna' 'àti magdalene lọ́dún 2018 wọ́n yàn án láti díje fún àmìn-ẹ̀yẹ fún amú... |
florence kíkẹ́lọmọ àjàyí nigerian football defender florence kíkẹ́lọmọ àjàyí jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin tí ó wà nínú ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin nàìjíríà nígbà kan rí ó ń gba bọ́ọ̀lù díje fún ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin dínamo guadalajara ní orílẹ̀-èdè spain alábala kejì iṣẹ́ kíkẹ́lọmọ bẹ̀rẹ̀... |
mike ezuruonye mike ezuruonye tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹsàn án ọdún 1982 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjị́ríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí mike ní ìlú uzoakoli ní ìpínlẹ̀ abia wọ́n bi ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹsàn án ọdún 1982 ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti federal government college ní ìlú w... |
fẹ́mi odùgbèmí fẹ́mi odùgbèmị́ tí wọ́n bí ní ọdún 1963 jẹ́ òǹkọ̀tàn àti olùya fọ́rán àwọn àkọsílẹ̀ láé láé adarí eré olùgbéré jáde àti ayàwòrán ọmọ orịlẹ̀-èdè nàìjírià iṣẹ́ rẹ̀ fẹ́mi odùgbèmị́ ni wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ montana state university níbi tí ó ti kọ́ nípa gbígbé eré àt... |
báyọ̀ adébọ̀wálé báyọ̀ adẹ́bọ̀wálé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 1944 jẹ́ akọ ewì òǹkọ̀wé ọ̀jọ̀gbọ́n lámèyítọ́ ònṣètò ìwé àti olùdásílẹ̀ ilé-ìwé african heritage library and cultural centre tí ó wà ní adéyipo ni ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ òyọ́ i ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ wọ́n bí adébọ̀wálé sí ìdílé bàbá rẹ̀ àkàngbé adébọ̀wàlé ... |
adéníkẹ̀ẹ́ grange nigerian politician adenike grange jẹ́ mínísítà àná fún ètó ìlera lórílẹ̀ èdè nàìjíríà láti ọdún 2007 sí 2008 ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ adéníkẹ̀ẹ́ grange kàwé ní ìlú èkó kí ó tó kọjá sí st francis' college letchworth ní united kingdom láti tẹ̀ síwájú ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó lọ́dún 1958 sí 1964 n... |
cynthia erivo english actress singer and songwriter cynthia onyedinmanasu chinasaokwu erivo tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kìíní ọdún 1987 jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò olórin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè england ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ nàìjíríà pọ́ńbélé ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmìn-ẹ̀yẹ pàápàá jù lọ àmìn-ẹ̀yẹ emmy tony... |
mojisola adeyeye mojisola christianah adeyeye jẹ́ onímọ̀ nípa òògùn àti ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ààrẹ orílẹ̀-èdè nàìjíríà muhammadu buhari yàǹ ań sí ipò olùdarí-gbogbogbò fún ilé iṣẹ́ tí ó ń rí sí ìṣàkóso óúnjẹ àti òògùn national agency for food and drug administration and control ní ọjọ́ kẹta oṣú kọkànlá ọdú... |
empress njamah empress njamah jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní ọdún 2012 wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ẹ̀yẹ best supporting actress láti ọ̀dọ̀ africa movie academy award ìgbésí ayé rẹ̀ àwọn òbí njamah jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti cameroon ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí olabisi onabanjo university nínú ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ... |
femi taylor femi taylor bíi ni ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin ọdún 1961 jẹ́ oníjó àti òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá oola tí ó kó nínú eré return of the jedi ní ọdún 1983 ó kó ipa tantomile nínú eré orin tí cats ni ọdún 1981 femi jẹ́ ìyàwó fún clauis skytte kamper ó sì ti bí ọmọ méjì |
moyo lawal moyọ̀ lawal jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó gbà àmì ẹ̀yẹ revelation of the year láti ọ̀dọ̀ nollywood awards ní ọdún 2012 ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí lawal sí ìlú badagry ó gboyè nínú ìmò creative arts láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí yunifásítì ìlú èkó iṣẹ́ ó kópa nínú ìdíje next movie star àmọ́ kò yeg... |
bọ́sẹ̀ ogulu nigerian academic and artist manager bọ́sẹ̀ ogulu jẹ́ onímò olùṣòwò ati alámòójútó ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ó bójú tó iṣẹ́ orin fún gbajú-gbajà olórin takadúfé burna boy tí ó tún jẹ́ ọmọ rẹ̀ òun ni gbogbo ènìyàn mò sí mama burna ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ ogulu jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ lámèyítọ́ olórin ilẹ̀ nàìj... |
nina sosanya oluwakemi nina sosanya bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 1969 jẹ́ òṣèré tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínú eré w1a àti last tango in halifax ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí sosanya sí ìlú islington ní london baba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ nàìjíríà ìyá rẹ sí jẹ́ ọmọ ilẹ̀ britain ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ vale of ca... |
rukky sanda rukayat akinsanya bíi ni kẹtàlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1984 tí orúkọ inagi rẹ̀ jẹ́ rukky sanda jẹ́ òṣèré àti adarí eré ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2004 nígbà tí ó ṣí wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí lagos state university óun àti òṣèré bọ́láńlé nínálowó jẹ́ mọ̀lẹ́bí |
folake olowofoyeku folake olowofowoyeku bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1983 jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó kópa nínú eré bob hearts abishola ní ọdún 2019 ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí olowofowoyeku sí ìdílé babatunji olowofowoyeku àti felicia olowofowoyeku bàbá rẹ̀ jẹ́ olóṣèlú ní ... |
khabirat kafidipe kabirah kafidipe jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí araparegangan fún ipa tí ó kó nínú eré saworoide ní ọdún 1999 èyí tí tunde kelani gbé jáde ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí kafidipe ní ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje ó jẹ́ ọmọ ìlú ikereku ní abẹ́òkúta ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ abeo... |
katung aduwak nigerian film producer director screenwriter katung aduwak tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹta ọdún 1980 jẹ́ ẹni tí ó jáwé olúborí nínú ìdíje big brother nigeria ní ọdún 2006 wọ́n bi ní ìlú zonkwa ní ìpínlẹ̀ kaduna ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ònkọ̀tàn olùgbéré-jáde àti olùdarí eré orí-ìtàgé as well ... |
kemi adesoye nigerian screen writer kẹ́mi adésọyè jẹ́ òǹkọ̀tàn tí ó kọ gbajú-gbajà eré the figurine ó sì tún ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré onípele lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán bí tinsel ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rè wọ́n bí adésọyè ní ìpínlẹ̀ kwara ni won to ni ipinle kaduna she is the last of four children adésọyè fẹ́ràn láti máa wo àw... |
sokari ekine sokari ekine jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà blogger àti oǹkọ̀wé ó ṣiṣẹ́ oníròyìn ní pambazuka news tí ó sìn ti kọ̀wé fún feminist africa àti new internationalist ekine ti fìgbà kan ní ìkànnì ìtakùrọ̀sọ ayélujára láàárín ọdún 2004 àti 2014 níbi tí ó ti máa ń tàkùrọ̀sọ nípa ẹ̀tọ́ obìnrin ẹ̀tọ́ ... |
fati lami abubakar nigerian judge fati lami abubakar tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 12 april 1951 jẹ́ adájọ́ àgbà ìpínlẹ̀ niger obìnrin àkọ́kọ́ fún nàìjíríà àti aya ààrẹ-àná abdulsalami abubakar lọ́dún 1998 sí 1999 ó di adájọ́ àgbà ní ìpínlẹ̀ niger lọ́dún 2013 sí 2016 ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀r... |
fati abubakar nigerian photographer fati abubakar jẹ́ gbajúmọ̀ oníròyìn aláwòrán àti afohùn-fawòrán ṣàgbékalẹ̀ ètò ó jẹ́ ọmọbìnrin ọmọ bíbí maiduguri ní ìpínlẹ̀ borno orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni bí ti o gbajúmọ̀ dé ìwé-ìròyìn the new york times cnn africa bbc àti voice of america ṣe àtẹ̀jádé iṣẹ́ rẹ̀ ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀... |
ifeoma onyefulu ifeoma onyefulu tí wọ́n bí lọ́dún 1959 oǹkọ̀wé ọmọdé oǹkọ̀wé ìtàn-àròsọ àti afẹ̀rọyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká nípa ìwé àwòrán rẹ̀ tí ó ṣe fi ṣe àfihàn ìgbésí ayé rẹ̀ abúlé rẹ̀ nílẹ̀ adúláwò afíríkà wọ́n bí ifeoma ní ìlú onitsha ní ìpínlẹ̀ anambra ní nigeriaó jẹ́ ọmọ bíbí ìra... |
viola onwuliri viola adaku onwuliri tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 1956 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ biochemistry àti olóṣèlú tí ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí aṣojú fún orílẹ̀-èdè nàìjíríà sí ilè òkèrè ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ viola jẹ̣́ àkọ́bí nínú àwọn ọmọ ọba eze cletus àti ugoeze dorathy oparaoji ti ìlú amuzi ní ìjọba ìbílẹ̀ ahi... |
abiodun duro-ladipo abíọ́dún dúró-ládípọ̀ jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní ọdún 1963 ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ eléré tí dúró ladipo gbé kalẹ̀ ó yege nínú ipa ọya tí ó kó nínú eré ọba kòso lẹ́yìn ikú ọkọ rẹ̀ ní ọdún 1978 abiodun tí kópa nínú orísìírísìí eré tí ó gbé àṣà àti ìṣe ilẹ̀ áfríkà sókè ó kó ipa moremi n... |
modupe adeyeye modúpé adéyeyè bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje ọdún 1992 jẹ́ òṣèré tí ó gbajúmọ̀ fún ipa faith olubunmi tí ó kó nínú eré eastenders àti blessing chambers nínú eré hollyoaks ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí sí ìlú london ó ti kópa nínú àwọn eré dírámà tí our girl my murder àti doctors ó kópa n... |
teni aofiyebi teniade aofiyebi jẹ́ òṣèré àti oníṣòwò lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kópa nínú eré mirror in the sun ní ọdún 1984 títí di ọdún 1986 ní ọdún 2003 ó kópa nínú eré for better for worse ní ọdún 2005 ó kópa nínú eré prince of savannah èyí tí bayo awala ṣe adarí fún ní ọdún 2013 ó kópa nínú eré ìfẹ́ flower girl èyí tí... |
bolanle awe bọ́láńlé fájẹ́m̄bọ́là awẹ́ tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1933 26 january 1933 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ ìtàn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ wọ́n bí bọ́láńlé lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1933 ní ilu ilesha orile-ede nàìjíríà oruko obi re je samuel akindeji fajemb... |
agnes osazuwa nigerian sprinter agnes osazuwa tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1989 26 june 1989 ní ìlú benin ìpínlẹ̀ edo jẹ́ eléré-ìjẹ lórí pápá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó máa ń díje fún nàìjíríà agnes ṣojú nigeria ní ìdíje òlímpíkì ti ọdún 2008 ní beijing lórílẹ̀-èdè china ó díje nínú eré gbagigbagi... |
desmond elliot desmond elliot ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kejì ọdún 1974 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé adarí eré àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti kópa nínú eré àti àwọn eré àtìgbà-dégbà onípele orí ẹ̀tọ amóhùn-máwòrán tí ó ti jú igba lọ ní orílẹ̀-èdè baba rẹ̀ ati ní òkè òkun ó ti gba amì-ẹ̀yẹ fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìt... |
sylvia oluchy ngozi sylvia oluchi ezeokafor tí a mọ̀ bi sylvya oluchy jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí sylvia oluchi ní ìlú èkó ó sì dàgbà ní ìlú àbújá o kẹ́ẹ̀kọ́ eré tíátà ní yunifásítì nnamdi azikiwe ti ìlú awka ìpínlẹ̀ anámbra iṣẹ́ ìṣe rẹ̀ gẹ́gẹ́bí ó ti ṣe sọ ìyá rẹ̀ n... |
yinka olukunga yínká olukunga tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ ọláyínká olukunga tí a sì mọ̀ sí nnenna jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti olùgbàlejò lóri ètò tẹlifíṣọ̀nù iṣẹ́ ìṣe rẹ̀ ó jẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́-gboyè láti yunifásitì ti ìpínlẹ̀ èkó ó sì gbajúmọ̀ fún ètò tẹlifíṣọ̀nù àwọn ọmọdé tí ó maá n ṣe lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ilé-iṣẹ́ wálé ad... |
ṣeun ọmọ́jọlà ṣeun ọmọ́jọlà tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ olúwaṣeun ọmọlará ọmọ́jọlà jẹ́ akọrin akọ̀wé orin àti òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà kan rí ó ti lo vilara gẹ́gẹ́ bi ìnagijẹ rẹ̀ nídi iṣẹ́ rẹ̀ ṣùgbọ́n ó padà wá pinnu láti maá lo orúkọ rẹ̀ gangan tí n ṣe ṣeun ọmọ́jọlà gẹ́gẹ́ bi akọrin àkọ́kọ́ orin àdákọ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ... |
lisa omorodion ọmọọba lisa omorodion tí a mọ̀ nídi iṣẹ́ rẹ̀ bi lisa omorodion jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà agbéréjáde àti olùṣòwò ó gbajúmọ̀ fún ipa iwájú rẹ̀ nínu fíìmù ti ọdún 2013 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ first cut pẹ̀lú àjọṣepọ̀ joseph benjamin àti monalisa chinda ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí omorodion ní ìlú l... |
rachel oniga rachel oniga tí a bí ní 23 oṣù kaàrún ọdún 1957 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ̀ ìṣe rẹ̀ rachel oniga wá láti agbègbè eku ní ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ṣùgbọ́n tí a bí ní èbútté mẹ́tta ìpínlẹ̀ èkó ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1993 ní kété tí ó pínyà pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ ó kọ́kọ́ ṣiṣẹ́ fún ì... |
fúnkẹ́ bucknor-obruthe funke bucknor-obruthe tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1976 27 june 1976 jẹ́ gbajúmọ̀ oníṣòwò àti amọ̀fin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni aláṣẹ àti olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ zapphaire events ó jẹ́ ọ̀kan lára gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká tí wọ́n kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ abánìṣètò ètò ló... |
georgina onuoha georgina onuoha jẹ́ òṣèré nollywood afẹwàṣiṣẹ́ olóòtú ètò tẹlifíṣọ̀nù àti afowóṣàánú ó wá láti ìpínlẹ̀ anámbra ní gúúsù ìla-òòrùn nàìjíríà ó darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ fíìmù ti nàìjíríà ní ọdún 1990 nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́wàá ṣùgbọ́n ó di gbajúmọ̀ ní ọdún 1992 lẹ́hìn kíkópa rẹ̀ nínu eré living in bondage wọ́n ... |
weruche opia reanne weruche opia tí a bí ní 11 oṣù kẹẹ̀rin ọdún 1987 ní nàìjíríà jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè bìrìtìkó ó sì tún jẹ́ olùṣòwò ó jẹ́ aláàkóso ilé ìtajà rẹ̀ tí ó dá sílẹ̀ táa pe orúkọ rẹ̀ ni jesus junkie clothing ìṣẹ̀mí rẹ̀ weruche gbajúmọ̀ fún kíkó ipa cleopatra ofoedo nínu er... |
cossy orjiakor cossy orjiakor tí a bí ní 16 oṣù kẹẹ̀wá jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà olùgbéréjáde akọrin àti oníjó ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn tí ó hàn nínu fídíò orin kan tí obesere ṣe àwọn awuye sì tún wà lóri pé ó maá n fí ọmú rẹ̀ hàn síta tí ó bá wà láàrin àwùjọ àti nígbà tí ó bá n ṣiṣẹ́ ijó rẹ̀ nínu fídíò o... |
tosyn bucknor olúwatósìn bucknor tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tosyn bucknor tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹjọ ọdún 1981ó sìn ta téru nípàá lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2018 15 august 1981 19 november 2018 jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ òṣèrébìnrin àti gbajúmọ̀ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lórí ìtàkùn abánidọ́rẹ̀ẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó l... |
mercy chinwo mercy chinwo jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin akọrin ajíyìnrere àti akọ̀wé orin ọmọ nàìjíríà òun ló gbàmìn ẹ̀yẹ ìdíje nigerian idol abala kejì ti ọdún 2012 ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí mercy nnenda chinwo lọ́jọ́ karùn-ún oṣù kẹsàn-án ọdún 1990 ní port harcourt ìpínlẹ̀ rivers ó jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ẹbí rẹ̀ ó bẹ̀rẹ... |
cynthia shalom cynthia shalom tí a bí ní 18 oṣù kẹẹ̀ta ọdún 1988 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà agbéréjáde àti olùṣòwò ó jẹ́ ajáwé olúborí níbi abala kọkànlá ti ètò next movie starláti ìgbà náà ló ti wá kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù nollywood ó kópa nínu eré alátìgbà-dégbà ti m-net kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́tinsel ìbẹ̀... |
ada ehi ada ogochukwu ehi tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1987 18 september 1987 simply known by her stage name jẹ́ akọrin ajíyìnrere oǹkọ̀wé orin àti òṣèrébìnrin ọmọ nàìjíríà nígbà tí ó wà lọ́mọdún mẹ́wàá ló ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ̀ nígbà tí ó gbe orin fún akọrin ọmọdé ẹgbẹ́ rẹ̀ tosin jegede láti ìgbà tí ... |
abimbola craig abimbola craig ti a bi ni ọjọ kẹta ọjọ kọkànlá oṣù 1986 jẹ oṣere nollywood ti naijiria ti o ṣe irawọ bi tiwalade ni arabinrin arabinrin ni transit lakọkọ o jẹ lati jẹ olupilẹṣẹ ti girl skiny ni transit ṣugbọn o pari ni jijẹ olori lati akoko 1 abimbola ti lọ siwaju lati kii ṣe iṣe nikan ṣugbọn o tun ti ṣe... |
barbara soky barbara soky tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ bara sokoroma jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti akọrin tẹ́lẹ̀rí tí ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn kíkópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ mirror in the sun ó sinmi iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ipa ní àwọn ọdún 80 àti 90 kí ó tó padà sí ní bá iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lọ ní... |
maureen solomon maureen solomon tí a bí ní 23 oṣù kejìlá ọdún 1983 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà kan tí ó ti kópa nínu àwọn eré ti nàìjíríà tó ti lé ní ọgọ́rin làkókò ìgbà tò fi n ṣiṣé òṣèré lọ́wọ́ ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ̀ rẹ̀ a bí solomon ní ìlú isuochi ìpínlẹ̀ ábíá níbi tí ó ti ka ìwé mẹ́fà àti ìwé mẹ́wàá rẹ̀ ní ilé... |
dolly unachukwu dolly unachukwu tí a bí ní 1 kọkànlá oṣù 1969 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà agbéréjáde ònkọ̀wé àti olùdarí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹni-ìṣáájú ti nollywood ó gbajúmọ̀ káárí orílẹ̀-èdè nàìjíríà gẹ́gẹ́ bi fadake akin-thomas nínu eré tẹlifíṣọ̀nù fortunes a bí dolly unachukwu ní ọdún 1969 sí ìdílé eléyàn m... |
tosin jegede tosin jegede tí wọ́n bí lọ́dún 1980 jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀dọ́mọdé obìnrin olórin ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ orin rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ lọ́dún 1986 ló gbé àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde ti o pè ní children arise ọmọ ọdún márùn-ún ló wà ní àkókò náà lẹ́yìn náà ó gbé àwo orin méjì mìíràn jáde tí ó pè ní l... |
maryam yahaya maryam yahaya jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó maá n ṣe àwọn eré kannywood ó gbajúmọ̀ fún kíkópa rẹ̀ nínu fíìmù taraddadi tí elnass ajenda jẹ́ olùdarí wọ́n yan maryam yahaya gẹ́gẹ́ bi òṣèré tí yóó gòkè àgbà lọ́jọwájú níbi ayẹyẹ city people entertainment awards ní ọdún 2017 ó tún rí yíyàn lẹ́ẹ̀kan si... |
diana yekinni diana yẹ̀kínnì jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ọmọ orílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì tó gbajúmọ̀ jùlọ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu fíìmù bíi ije àti lunchtime heroes diana tún gbajúmọ̀ fún kíkó ipa genevieve nínu eré tẹlifíṣọ̀nù jenifa's diary ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú fúnkẹ́ akíndélé ní ọdún 2014 wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ti òṣèré... |
annabella zwyndila annabella zwyndila jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ káàkiri gẹ́gẹ́ bi ms green ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí annabella zwyndila ní ̀ilú ìbàdàn orílẹ̀-èdè nàìjíríà bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti nàìjíríà ìyá rẹ̀ sì jẹ́ òṣíṣẹ́ àgbà nídi ṣíṣe ètò ẹ̀kọ́ àwọn ará ìlú ó lọ sí ilé-ìw... |
eve esin eve esin jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà kan tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ ti city people entertainment awards fún ẹ̀ka ti òṣèrébìnrin tó ní ìlérí jùlọ ni nàìjíríà ní ọdún 2015 àmì-ẹ̀yẹ ti amaa fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ àti àmì-ẹ̀yẹ amvca fún ti òṣèrébìnrin tó dára jùlọ nínu eré ìtàgé ìbẹ̀rẹ̀ ayé... |
mayowa nicholas nigerian model máyọ̀wá nicholas tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1998 22 may 1998 jẹ́ gbajúmọ̀ aránṣọ-ṣoge ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni aránṣọ-ṣoge ọmọ nàìjíríà àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣàfihàn ní níbi ipàtẹ oge ti dolce gabbana saint laurent àti calvin klein iṣẹ́ máyọ̀wá nicholas wà lára àwọn ... |
chelsea eze chelsea eze tí a bí gẹ́gẹ́ bi chelsea ada ezerioha ní 15 oṣù kọkànlá jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ pẹ̀lú kíkópa nínu àkọ́kọ́ fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ silent scandals ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú genevieve nnaji àti majid michel fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù náà ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ níb... |
ibinabo fiberesima ibinabo fiberesima tí a bí ní 13 oṣù kínní ọdún 1970 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti olùṣàkóso ìdíje ẹwà tẹ́lẹ̀rí ó ti fi ìgbà kan jẹ́ ààrẹ ẹgbẹ́ actors guild of nigeria ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí ibinabo sí ọwọ́ bàbá tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ìyá tí n ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè... |
bikiya graham-douglas bikiya graham-douglas jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọmọbìnrin àwọn tọkọtaya olóṣèlú nàìjíríà kan alabo graham-douglas àti bolere elizabeth ketebu graham-douglas ti kẹ́kọ̀ọ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga bíi london academy of music and dramatic art oxford school of drama bridge theatre training ... |
keira hewatch keira hewatch tí a bí ní 8 oṣù kọkànlá ọdún 1985 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrin àti ònkọ̀wé tó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ gẹ́gẹ́ bi 'keche' nínu fíìmù two brides and a baby àti fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi 'peace nwosu' nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ lekki wives hewatch ti gba àmì ẹ̀yẹ best of nollywo... |
hafsat idris hafsat ahmad idris tí a tún mọ̀ sí hafsat idris táa bí ní 14 oṣù keèje ọdún 1987 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó maá n ṣiṣẹ́ lágbo òṣèré ti kannywood eré àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ti kópa ni fíìmù barauniya 2016 ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jùlọ ní ọdún 2019 ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ hafsat jẹ́ ọm... |
adeola olubamiji adéọlá deborah olúbámijí jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ ti ìlú naijiria ati kanada tí ó ṣe àmọ̀já ní ìṣelọ́pọ̀ irin àti ṣiṣu tí a tún mọ̀ ní atejade-3d ní ọdún 2017 adéọlá jẹ́ ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ tí ó gba phd nínu ìmọ̀-ìṣe biomedical lati ilé-ẹ̀kọ́ gíga university ti saskatchewan ní ìlú canada ó sì tẹ̀síwájú láti fún... |
àdùní adé nigerian actress and model àdùní adétí ó jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti módẹ́ẹ̀lì ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1976 ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí àdùní ní ìlú new york ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìlú irish láti orílẹ̀-èdègermany nígbà tí bàbá rẹ̀ jẹ́ yorùbá ọmọ bíbí or... |
demi isaac oviawe demi isaac oviawe tí a bí ní 2 oṣù kọkànlá ọdún 2000 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní orílẹ̀-èdè ireland ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi linda walsh nínu eré the young offenders tí ọdún 2018 oviawe dàgbà ní ìlú mallow orílẹ̀-èdè ireland sí ọwọ́ àwọn òbí rẹ̀ àwọn òbí oviawe dìídì sọ́ ló... |
oghenekaro itene oghenekaro lydia itene jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti olùṣòwò ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ oghenekaro itene wá láti ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ṣùgbọ́n wọ́n bi ní ìlú benin ìpínlẹ̀ ẹdó níbi tí ó dàgbà sí ó jẹ́ akẹ́kọ-gboyè láti ilé-ìwé gíga yunifásítì ìlú benin òun ni àbígbẹ̀yìn nínu àwọn ọmọ mẹ́fà ti òbí rẹ̀ àkọ́kọ́ ṣíṣ... |
carol king actress carol king tí a bí ní 24 oṣù keèje ọdún 1963 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ bi jùmọ̀kẹ́ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ everyday people carol jẹ́ ẹnìkan tí ó maá n sábà kó ipa ìyá lọ́pọ̀lọpọ̀ nínu àwọn eré ó sì ti ṣe bẹ́ẹ̀ hàn nínu àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù àti... |
fọlákẹ́ akínyẹmí nigerian-norwegian sprinter fọlákẹ́ akínyẹmí tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1999 31 march 1990 jẹ́ gbajúmọ̀ a sáré-ìjẹ fún orílẹ̀-èdè norway ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká eléré ìwọ̀n mítà ọgọ́rùn-ún àti igba ìgbésí ayé iṣẹ́ rẹ̀ ... |
alex lopez òṣèrébìnrin alexandra lópez tí a mọ̀ sí alex lopez jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè brasil tí ó jẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀rí ó gbajúmọ ̀jùlọ fún ipa kan tí ó kó nínu fíìmù amẹ́jọ́lọ́wọ́ kan táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní domitila 2 ní ọdún 1993 ó ṣe ipò kejì níbi ìdíje ẹwà most beautiful girl in niger... |
uche mac-auley uche mac-auley tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ uchechukwu nwaneamaka tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ bi uche obi osotule jẹ́ gbajúgbajà òṣèré ònkọ̀wé olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ mac-auley wá láti ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ní nàìjíríà àwọn òbí mac-auley jẹ́ olùkọ́ tí wọ́n sì maá n ṣiṣẹ́ káàkiri nítorí ... |
francis agu francis agu tàbí francis okechukwu agu jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé sinimá ati orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán ọmọ ń orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejì ọdún 1965 ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó ní eré onípele àtìgbà-dégbà tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ̀ ní orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní... |
annie macaulay-idibia annie macaulay-idibia tí a bí ní 13 oṣù kọkànlá ọdún 1984 jẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ àti òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó dára jù níbi ayẹyẹ best of nollywood awards ti ọdún 2009 ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí annie ní ìbàdàn ṣùgbọ́n ó wá láti ìlú eket ní ìpín... |
adéńrelé ṣónáriwo adéńrelé ṣónáriwo jẹ́ gbajúmọ̀ oníṣòwò àti atọ́kùn nǹkan ìṣẹ̀m̀báyé àti iṣẹ́-ọ̀nà òun ni olùdáaílẹ̀ ilé-iṣẹ́ iṣẹ́-ọ̀nà rele art gallery tí ó wà ní military street onikan erékùṣù èkó ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ nàìjíríà òun ni olórí atọ́kùn ìṣẹ̀m̀báyé fún tó ṣojú nàìjíríà lọ́dún 2017 níbi ìpàtẹ venice bienn... |
tayanna tayanna ojoibi 29 september 1984 chernivtsi ìsọ̀kan sófìẹ̀tì je olorin omo ile yukréìn |
william sanderson william sanderson january 10 1944 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
samantha biffot samantha biffot tí a bí ní ọdún 1985 jẹ́ ònkọ̀tàn eré olóòtú àti olùdarí eré ọmo orílẹ̀-èdè-gàbọ̀n àti orílẹ̀-èdè faransé ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ a bí biffot ní ìlú párìsì ní ọdún 1985 ó jẹ́ aláṣá púpọ̀ nítorí liló igbà èwe rẹ̀ ní àwọn ìlú bíi gàbọ̀n gúúsu kòríà àti fránsì èyí ti ́ó padà nípa lóri ṣíṣe iṣẹ́ òṣèré... |
angela aquereburu angela aquereburu tí a bí ní 11 oṣù kíní ọdún 1977 jẹ́ oǹkọ̀tàn olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè tógò ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ aquereburu ni a bí ní tógò sí ọwọ́ ìyá tí ó wá láti guadeloupe orílẹ̀-èdè faransé ó ní ìfẹ́ sí eré ṣíṣe láti ìgbà èwe rẹ̀ ó lọ ilé-ìwé ní tógò àti pointe-a-pitre ní guad... |
amal bedjaoui amal bedjaoui tí a bí ní 27 oṣù keèje ọdún 1963 jẹ́ olùdarí eré agbéréjáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè àlgérià a bí bedjaoui ní algiers ó sì kẹ́kọ̀ọ́ fíìmù ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga new york university ó parí ní ẹ̀ka institut des hautes études cinématographiques ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà lẹ́hìn náà ó gba oyè gíg... |
ken erics nigerian actor ekenedilichukwu ugochukwu eric nwenweh tí àlàjẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ ken erics ugo tàbí ken erics jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti ọ̀kọrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré sinimá kan tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ the illiterate eré tí òṣèrébìnrin tonto dikeh àti ... |
carole karemera carole umulinga karemera tí a bí ní ọdún 1975 jẹ́ òṣèré oníjó àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè rwanda ọ̀rọ̀ ayé rẹ̀ a bí karemera ní ọdún 1975 ní ìlú brussels nígbà èwe rẹ̀ karemara jáfáfá nínu ìmọ̀ ìṣirò ó sì maá n gbàá lérò láti ṣí ilé-iṣẹ́ búrẹ́dì karemera kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ national conservatory of th... |
tana adélànà nigerian actress christiana nkemdilim adélànà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tana adelana tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejìlá ọdún 1984 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò olóòtú afẹ̀wàṣojú atọ́kùn ètò tẹlifíṣàn àti oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó gbàmìn ẹ̀yẹ ammúgbalẹ́gbẹ̀ẹ́ olú-ẹ̀dá-ìtàn ti city pe... |
chiwetalu agu nigerian actor chiwetalu agu jẹ́ ògbóntagì òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọdún 1956 ó jẹ́ aláwàdà ati olùgbéré-jáde tí ó gba amì-ẹ̀yẹ ti òṣèré kùrin tó peregedé jùlọ nínú eré ìbílẹ̀ níbi ìsàmì ayẹyẹ nollywood ní ọdún 2012 àwọn ọlọ́kan-ò-jọkan ìpèdè rẹ̀ tí ó ma ń lò nínú eré ni ó sọọ... |
françoise ellong françoise ellong tí a bí ní 8 oṣù kínní ọdún 1988 jẹ́ olùdarí fíìmù àti ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù ìsẹ̀mí rẹ̀ a bí ellong ní ìlú douala orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù ní ọdún 1988 nígbà tó wà lọ́mọdún mọ́kànlá ó gbé pẹ̀lú mọ̀lẹ́bí rẹ̀ kan ní ìlú brunoy níbi tí ó ti kọ àkọ́kọ́ ìtàn rẹ̀ ellong ḱopa nínu ìdíj... |
christiane chabi-kao christiane chabi-kao tí a bí ní 30 oṣù kẹẹ̀fà ọdún 1963 jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè benin ìsẹ̀mí ayẹ́ rẹ̀ a bí chabi-kao ní ìlú marseille orílẹ̀-èdè fránsì ní ọdún 1963 ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga university of reims champagne-ardenne láti ọdún 1984 si 1986 ní ọdún 1990 chabi-kao padà sí... |
magaajyia silberfeld sarah magaajyia silberfeld tí a bí ní 30 oṣù kẹẹ̀jọ ọdún 1996 jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè nijer àti fránsì ìsẹ̀mí rẹ̀ silberfeld jẹ́ ọmọ sí olùdarí eré táa mọ̀ sí rahmatou keïta àti oníṣẹ́ ìròyìn antoine silber ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé ní agbègbè rẹ̀ nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mọ́kànl... |
roukiata ouedraogo roukiata ouedraogo tí a bí ní 1979 jẹ́ ònkọ̀tàn òṣèré àti apanilẹ́ẹ̀rín ọmọ orílẹ̀-èdè bùrkínà fasò ìsẹ̀mí rẹ̀ roukiata dàgbà ní ìlú fada n'gourma ó jẹ́ ọmọbìrin ti òṣìṣẹ́ ìjọba kan bàbá rẹ̀ náà ti kópa rí nínu eré ìtàgé nígbà tí ó wà lọ́mọdé ouedraogo lọ sí ìlú ouagadougou láti tẹ̀síwájú nínu ẹ̀kọ́ ... |
mariam kaba mariam kaba tí a bí ní 9 oṣù kẹẹ̀jọ ọdún 1961 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè fránsì àti guinea ìsẹ̀mí rẹ̀ a bí kaba ní ìlú kankan orílẹ̀-èdè guinea ó jẹ́ ọmọbìnrin mohamed ba kaba ó kó lọ sí orílẹ̀-èdè fránsì ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1980 lẹ́hìn tí ó parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ kaba forúkọsílẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ école des... |
awa sène sarr awa sène sarr jẹ́ òṣèrébìnrin àti apanilẹ́ẹ̀rín ọmọ orílẹ̀-èdè sẹ̀nẹ̀gàl isẹmi rẹ awa sène sarr lẹnìkan tí ó ní ìfẹ́ sí láti di amòfin tó sì ṣe bẹ́è kẹ́kọ̀ọ́ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga yunifásitì ìlú dakar lẹ́hìn náà ó forúkọsílẹ̀ láti kẹ́kọ̀ọ́ eré ṣíṣe ní national institute of arts of dakar ní orílẹ̀-èdè sẹ̀... |
ego boyo nwakaego ego boyo bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹsàn-án ọdún 1968 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá anne haastrup nínú eré checkmate òun ni ààrẹ fún ẹgbẹ́ international women society iws èyí tí wọ́n gbé kalẹ̀ ní ọdún 1957 ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ enugu ó jẹ́ ìyàwó fún omamofe boyo tí ó jẹ́ ìkan láàrin àw... |
samantha mugatsia samantha mugatsia tí a bí ní ọdún 1992 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè kẹ́nyà ìsẹ̀mí rẹ̀ a bí mugatsia ní ọdún 1992 ó jẹ́ ọmọ grace gitau ó dàgbà ní ìlú nairobi ó sì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ẹgbẹ́ àyàn kan tí wọ́n pè ní the yellow machine ó tún ti jẹ́ afẹwàṣiṣẹ́ nígbà kan rí mugatsia kẹ́kọ̀ọ́ ìmòfin ní ilé-ẹ̀kọ́ gí... |
nicole amarteifio nicole amarteifio tí a bí ní ọdún 1982 jẹ́ agbéréjáde olùdarí àti ònkọ̀tàn eré ọmọ orílẹ̀-èdè ghánà ìsẹ̀mí rẹ̀ a bí amarteifio ní orílẹ̀-èdè ghánà ṣùgbọ́n ó gbé ní ìlú lọ́ndọ̀nù fún ọdún mẹ́fà láti ìgbà tí ó fi wà lọ́mọ oṣù mẹ́ta nítorí ìfipágbàjọba tí ó ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè rẹ̀ ó padà tún kúrò ní ìlú ... |
tope tedela temitope christopher tedela tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tọ́pẹ́ tedela jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí tọ́pẹ́ gẹ́gẹ́ bí àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀ sí ìlú èkó àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkìtì ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ girama ti model college tí ó wà ní ì... |
aminu shariff aminu aliyu shariff tí a tún mọ̀ sí aminu momoh ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 1977 l jẹ́ adarí eré ònkọ̀tàn olùgbéré-jáde ati oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán olóòtú ìwé ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ aminu shariff's filmography awards list of awards received by aminu aliy... |
rabilu musa rabilu musa tí gbogbonènìyàn mọ̀ sí dan ibro tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejìlá ọdún 1971 jẹ́ ògbóntagì òṣèré aláwàdà olùgbéré-jáde àti adarí eré hausa ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni wọ́n ń pè ní asíwájú ati olùdásílẹ̀ agbo kannywood òin náà tún ni ó tún mọ awàdà ṣe jùlọ nínú gbogbo awọn òṣèré aláwàdà ní ... |
nadia fares anliker nadia fares anliker tí a bí ní 18 oṣù kẹẹ̀sán ọdún 1962 jẹ́ olùdarí àti ònkọ̀tàn eré ọmọ orílẹ̀-èdè ìjíptì àti swítsàlandì ìsẹ̀mí rẹ̀ a bí fares ní ìlú bern orílẹ̀-èdè swítsàlandì bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè ìjíptì tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè swítsàlandì ó kọ́ èdè èdè lárúbáwá ní àkókò tí ó n k... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.