raw_text
stringlengths
2
128k
irène tassembédo irène tassembédo ti a bi ni ojo kankandilogun osu kejo odun 1956 je onijo akorin ati osere ti o wa lati orile ede bùrkínà fasò igbesiaye o ko ijo ibile titi ouagadougou lehin na o ko ijo imusin titi ile europe lehin germaine acogny ni ile iwe mudra afrique ti maurice bejart da sile ni dakar bbnxnxxmxnm...
dakore egbuson-akande dakore egbuson-akande tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ń jẹ́ dakore omobola egbuson jẹ́ òṣèré nigeria ó jẹ́ aṣojú fún amnesty internation amstel malta àti oxfam ní america igbesiaye ìpínlẹ̀ bàyélsà ni wọ́n bí dakore si gẹ́gẹ́ bíi àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀ ó lọ sí ilé-ìwé corona àti ilé-ìwé ìjọba àpapọ̀ fún àwọn ọmọ ...
fatoumata coulibaly fatoumata coulibaly jẹ oṣere fiimu ara ilu málì adari akọroyin ati ajafẹtọ ẹtọ awọn obinrin ni pataki julo ko gba di da abe fun awon omobirin igbesi aye ibẹrẹ fatoumata coulibaly wa lati ebi awon olorin iya-iya e bazeko traore je olorin lati apa sikasso ibi ti coulibaly ti wa coulibaly koko sise geg...
dayo okeniyi ọládayọ̀ a òkéníyì tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹfà ọdún 1988 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti àti sinimá ọmọ oeílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n bí sí orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà òun ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tresh látàrí ipa rẹ̀ tíó kó nínú eré 'the hunger games' òun náà tún ni ẹ̀dá ìtàn and danny dyson nínú eré terminator geni...
afeez oyetoro afeez oyétòrò tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù kẹjọ ọdún 1963 jẹ́ adérín-pòṣónú òṣèré sinimá àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí sàká ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí afeez ní ìlú ìsẹ́yìn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè akọ́kọ́ àti èkejì nínú ìmọ̀ theatre...
fatoumata diawara fatoumata diawara tí wọ́n bí ní ọdún un 1982 ní ivory coast jẹ́ òṣèré olórin àti akọ-orin tí a ti yàn lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà fún àmì-ẹ̀yẹ grammy award ó wá láti orílẹ̀-èdè málì wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀ lẹ́ẹ̀mejì fún grammy award titi ogótalélọ́kan fún awo orin agbaye ti o da ju fún àwo orin rẹ̀ fenfo àti fún...
fred amata nigerian actor producer and director fred amata jẹ́ òṣèré olùgbéré-jáde àti adarí eré ọmọorílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kẹ́kòọ́ gboyè ìmọ̀ nínú ìmọ̀ eré oníṣẹ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásitì jos ó di ìlú-mòọ́ká ní ọdún 1986 nínú eré legacy òun ni ààrẹ fún directors guild of nigeria láti inú oṣù kejì ọdún 2016
bovi bovi jẹ́ aláwàdà òṣèré àti ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti gbé ètò man on fire kan tó gbajúmọ̀ jákè-jádò agbáyé ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ bovi ugbona ni wọ́n bí nu ìlú bìní tí ó jẹ́ olú ìlú fún ìpínlẹ̀ ẹdó ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti uniben ní ọdún 1991 ó tún wọlé sílé-ẹ̀kọ́ ti ìjọba àpapọ̀ ìlú ugheli...
remi abiola nigerian film actress and spouse of nigerian president moshood abiola rẹ̀mí abíólá oṣù kẹẹ̀jọ ọdún 1953 - oṣù keèje ọdún 2009 jẹ́ òṣèré fiimu ti ìlu nàìjíríà àti ìyàwó olóògbé moshood abíola ẹni tí ó ṣe pàtàkì nínú olùṣòwò àti olósèlú ìlú nàìjíríà rèmi kú sí ìlu new york ní ọjọ́ mókàndínlógbòn oṣù keèje ọdú...
nneka j adams nneka julie adams tí a bí ní 8 oṣù kẹẹ̀jọ tí a mọ̀ ní akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi nneka adams tàbí nneka j adams jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà tí ó wà ní ìlu kánádà ònkọ̀wé fiimu ó sì n ṣe fiimu orúkọ rẹ̀ tan dáada jùlọ fún àwọn ipa rẹ̀ tó kó nínu àwọn fiimu bí black men rock flight last to abuja àti nation under sie...
shuga
chet anekwe chet anekwe jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí a tọ́ dàgbà ní ìlú new york ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ò ti ṣe àwọn iṣẹ́ oríṣiríṣi káàkiri láti hollywood tí ó fi mọ́ nollywood pẹ̀lú tíátà ti ìlú new york
aderounmu adejumoke nigerian actress adéjùmọ̀kẹ́ adéróunmú jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà kan tí a bí ní abẹ́òkúta ìpínlẹ̀ ògùn nàìjíríà níbití ó ti ní ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ìwé gíga orúkọ rẹ́ tàn dáada jùlọ fún ṣíṣeré ipa gẹ́gẹ́ bi esther àti kelechi nínu àwọn gbajúmọ̀ eré tẹlifíṣọ́nù nollywood tí n ṣe jenifa's diary à...
toyin afolayan tóyìn afoláyan ọjọ́ìbí ọjọ́ 24 osù kẹsàn-án ọdún 1959 tí gbogbo ènìyán mọ̀ sí lọlá ìdíje jẹ́ òṣèré onítíátà nàìjíríà lóbìnrin àti àntí fún òṣèré onítíátà nàìjíríà lọ́kùnrin kúnlé afọláyan ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́hìn tí ó kópa pàtàkì gẹ́gẹ́ bi madam àdìsá nínu fiimu 1995 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ deadly affair
yvonne jegede yvonne jegede jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré-jáde model àti adarí ètò lórí ẹrọ amóhù-máwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́gẹ́dẹ́ di ìlú-mòọ́ká látàrí eré kan tí ó gbé jáde tí ó pè ní 3 is company ó di ẹni ayé ń fẹ́ lẹ́yìn tí ó kópa nínú fọ́rán àwo orin african queen tí gbajú-gbajà olótin 2face idibia àti anni...
paul igwe nigerian film director paul igwe wọ́n bí paul igwe ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1977 òun ni olùdásílẹ̀ whitestine cinema ó jẹ́ olùgbéré-jáde ònkọ̀wé àti ẹni tí ó gba amì-ẹ̀yẹ fún dídarí ètò orí ẹrọ amóhù-máwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ó ni eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkólé rẹ̀ ń jẹ́ clinic matters...
toyin abraham
bísí kọ́mọláfẹ́ bísí kọ́mọláfẹ́ tí a bí ní inú ọdún 1986 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùdarí eré olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà bísi di ìlú-mòọ́ká lẹ́yìn tí ó kópa nínú eré ìgboro ti dàrú àti aramotu igboro ti daru and aramotu ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ bísi ni ó jẹ́ àbílé kejì àwọ òbí rẹ̀ nínú àwọn ọmọ márùn ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí...
tomi odunsi tomi odunsi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1987 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olórin òńkọrin tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ṣaléwá nínú eré onípele ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ti tinsel ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí tómi ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1987 ní ìpínlẹ̀ ògùn ó lọ sílé ẹ̀kọ́ yunifásitì ìpínlẹ̀ èkó níbi tí...
afro candy afro candy tí a tún kọ ní afrocandy jẹ́ òṣèré fiimu tí ìlu nàìjíríà olùdarí eré akọrin afẹwàṣiṣẹ́ àti òṣèré oníhòhò ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti alákòso ti àwọn invisible twins productions llc ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ afro candy ní a bí ní umuduruebo ugiri-ike ìjọba agbègbè ikeduru ti ìpínlẹ̀ ímò nígbà tó wà lọ́mọd...
ijeoma grace agu nigerian actress ijeoma grace agu jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà kan ó jẹ ànfàní yíyàn fún òṣèré lóbìnrin tí ó dára jùlọ ní ipa àtìlẹyìn ní bi 12th africa movie academy awards ó tún gba ẹ̀bun òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ ní bi 2014 best of nollywood awards ní ọdún 2007 ó ṣe ìfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ lójú amóhù-máwòran ní...
pombajira pombajira pombogjira pambujira pombujira pombojira bombogira pombagira tabi inzila em ninu itan aye atijọ ti bantu ijosin rẹ yatọ pẹlu diẹ ninu awọn ile ti o ṣe akiyesi rẹ bi ọlọrun ati awọn ọmọ rẹ ti ipilẹṣẹ nipasẹ rẹ ati ni awọn miiran bi nkan eyiti o wọ inu iranran ti ohun-ini ni awọn eniyan ti a ko yà si ...
mmabatho montsho mmabatho montsho bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1983 jẹ́ akọ̀wé òṣèré àti adarí eré fíìmù ni orílẹ̀ èdè south áfríkà wọ́n bíi sì ìlú soweto ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ greenside high school kí ó tó tẹ̀ ṣíwájú sì ilẹ̀ ẹ̀kọ́ gíga tí university of south africa níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò audio-visual mult...
zenande mfenyana zenande mfenyana bíi ni ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 1985 jẹ́ òṣèré àti mọ́dẹ́lì ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó gbajúmọ̀ fún ipá noluntu memela tí ó kó nínú eré generations wọ́n bíi mfenyana sì ìlú johannesburg ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ queenstown girl's high school kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí univers...
nkhensani manganyi nkhensani manganyi jẹ́ òṣèré àti aránṣọ ni orílẹ̀-èdè south africa iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2000 manganyi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ aránṣọ tirẹ̀ tí ó pè ní stoned cherrie ìkan lára àwọn aṣọ tí ó rán gbáyi láti ilé iṣẹ́ ìròyìn drum ilẹ̀ iṣẹ́ náà má ń ṣe gíláàsì fún ojú díè nínú àwọn iṣẹ́ rẹ sì wà ní fashion institute o...
fúnmi martins fúnmi martins tí wọ́n bí ní ìlú iléṣà ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní inú oṣù kẹsàn án ọdún 1963 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí fúnmi ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní inú oṣù kẹsàn án ọdún 1963 ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ òkè-ọnà àti ilé-ẹ̀kọ́ girama ní ìlú a...
bubu mazibuko bubu mazibuko je òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó kọ ipa betsy nínú eré catch a fire ni ọdún 2006 ó kọ ipa thuli nínú eré gaz'lam 2002-2005 èyí sì lọ jẹ́ kí wọn yàán fún òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ duku duku awards fún ipá lindiwe tí ó kó nínú eré man on ground 2011 ni wọn ṣe yàán fún òṣèré tí...
bukky ajayi zainab bukky àjàyí 2 osù keèjì 1934 6 osù keèje 2016 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbé ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ bukky àjàyí ní a bí ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣùgbọ́n ó parí ẹ̀kọ́ gíga rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè england united kingdom pẹ̀lú àtìlẹyìn síkọ́láshípù ìjọba àpapọ̀ kan ní ọdún 1965 ó kúrò ní england wá sí nàìjírí...
fisayo ajisola fisayo ajisola ti a tun mọ ni freezon jẹ oṣere tẹlifisiọnu ati oṣere fiimu awoṣe ati akọrin oruko re tan daada julọ fun ipa rẹ ninu ere tẹlifisiọnu naijiria kan jenifa's diary pelu ajosepo funke akindele oruko re tun tan fun awọn ipa rẹ ninu awon ere tẹlifisiọnu this life nectar shadows burning spear cir...
aremu afolayan aremu afolayan jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó tún jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún òsèrékùrin kunle afolayan tí ó jẹ́ òṣèré àti adarí eré tí ó gba amì-ẹ̀yẹ adarí eré tó peregedé jùlọ ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ àrẹ̀mú afọláyan jẹ́ ọmọ bíbí gbajú-gbajà adarí eré àti olùgbéré-jáde adé love tí ó jẹ́ ọmọ ìlú ì...
mide funmi martins
afeez owó afeez abíọ́dún tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá olùgbéré-jáde àti adarí eré yorùbá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n fun ní ìnagijẹ rẹ̀ ọwọ́ látàrí bí ó ṣe jẹ́ ọlọ́wọ́-ọ̀rmtún àti ọ̀rẹ́ tímọ́ tímọ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé kan yẹmí ayébọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí afeez ní ìlú ...
bùkólá adéẹyọ̀ bùkọ́lá adéẹ̀yọ̀ jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré jáde adarí eré àti àsojú fún ilé iṣẹ́ kan ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí bùkọ́lá ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá ọdún 1989 ní ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ati girama ní ní ìpínlẹ̀ ògùn ó tún lọ sí ilé...
rẹ̀mí abíọ́lá nigerian film actress and spouse of nigerian president moshood abiola rẹ̀mí abíọlá tí wọ́n bí ní oṣù kẹwàá ọdún 1953 tí ó jáde láyé ní oṣù keje ọdún 2009 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré-jáde ati adarí eré sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ìyàwó moshood abíọlá rẹ̀mí papò dà ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹj...
hassanat akínwandé hassanat táíwò akínwándé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì ọdún 1960 tí a mọ̀ sí stage name wùnmí jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí ó ti kópa nínú eré ati sunimá oríṣiríṣi iṣẹ́ rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ré gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ní ọdún 1980 nígbà tí ó kópa nínú eré onípele ti ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkọ́l...
bọ́sẹ̀ àlàó nigerian nollywood actress and producer bọ́sẹ̀ àlàó ọmọtóyọ̀sí tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kíní ọdún 1985 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá olùdarí eré ati olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí bọ́sẹ̀ ní ìpínlẹ̀ èkó tí ó sì jẹ́ àbílé kẹrin nínú ẹbí rẹ̀ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ c...
kemi lala akindoju nigerian actress kẹ́mi lala akindoju jẹ́ òṣèrè ọmọ nàìjíríà kan ó gba ẹ̀bun africa magic kan fún ipa rẹ̀ nínu àṣàmùbádọ́gba fiimu dazzling mirage ìgbé ayé rẹ̀ a bí akindoju ní ọjọ́ 8 oṣù kẹẹ̀ta ọdún 1987 ní ìdílé àwọn ọmọ mẹ́rin ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ondo ó lọ ilé-ìwé girama ti queen's college ìpínlẹ̀ è...
ogun abẹ́lé ogun abẹ́lé jẹ́ ogun láàárín àwọn ẹgbẹ́ tó ṣètò láàárín ìpínlẹ̀ kan náà tàbí orílẹ̀-èdè èrò tí ẹgbẹ́ kan lé jẹ̀ẹ́ lá̀ti gba iṣàkóso orílẹ̀-èdè tàbí agbègbè kan lá̀ti gba om̀inira fún agbègbè kan tàbí láti yí àwọn ètò ìmúlò ìjọba padà òrò náà jẹ́ calque ti latin bellum civile èyí tí a lò láti tọ́ka sí ọ̀pọ̀l...
esther audu nigerian actress esther ene audu tí wọ́n bí ní ọjó kejìlélógún oṣù keta ọdún 1986 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ati sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà she is popularly known for starring in the films dinner 2016 mystified 2017 and order of the ring 2013 ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀tò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí esther ní ọjọ́ kejìlélógún oṣ...
chizzy alichi chigozie stephanie alichi tí a bí ní ọjọ 23 oṣù kejìlá ọdún 1993 tí a mọ̀ ní chizzy alichi jẹ́ òṣèré fiimu tí ìlu nàìjíríà ìgbé ayé rẹ̀ chizzy alichi wá láti ezza nkwubor nike ní enugu east ìjọba agbègbè kan nàìjíríà enugu nàìjíríà àbìkẹ́hìn ló jẹ́ nínú àwọn méjì tí òbí rẹ́ bí ìròyìn rẹ̀ kàn jákèjádò nígb...
liz anjorin nigerian actress and movie producer liz aishat anjorin ti a bi elizabeth aishat anjorin orukọ akọkọ ti a kọ ni ọna miiran si je lizzy jẹ oṣere ara ilu naijiria kan ẹniti o ṣe ẹya pupọ julọ ni ile-iṣẹ fiimu ti yorùbá o ti gba ami eye oṣere ti o dara julọ ni ti ẹbun awọn ọdọ awọn aṣeyọri ni ọdun 2012 awọn eni...
uzoamaka aniunoh nigerian actor uzoamaka doris aniunoh jẹ́ ònkọ̀wé àti òṣèré ará ìlu nàìjíríà ó ti di òdú tí kìń ṣe àìmọ̀ fólóko nínu eré mtv shuga léyìn tí ó ti hàn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà eré tẹlifíṣọ́nù náà tó fi mọ́ àkọ́kọ́ àti ẹ̀kẹfà ìgbé ayé rẹ̀ aniunoh ni a bí ní onitsha ó kẹ́ẹ̀kọ́ yunifásitì ti nàìjíríà ní ílu ...
eucharia anunobi nigerian actress producer and pastor eucharia anunobi tí a bí ní 25 oṣù karùn-ún 1965 jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà olùgbéréjáde àti pásítọ̀ ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínu fiimu abuja connection ó rí yíyàn níbi 2020 africa magic viewers’ choice awards fún ẹ̀bun òṣèré tó peregedé jùlọ ní ipa àtìlẹyìn nínu fiimu t...
funlola aofiyebi-raimi fúnlọ́lá aòfiyèbí-ràímì tí a àbísọ rẹ̀ jẹ́ abibat olúwafúnmilọ́lá aòfiyèbí ṣùgbọ́n tí a mọ̀ pẹ̀lú ìnagijẹ gẹ́gẹ́ bi far jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà ó ti ní ìfihàn rédíò fún ìgbà pípẹ́ ó farahàn nínu fiimu the figurine tinsel àti mtv shuga ìgbé ayé rẹ fúnlọ́lá ni ọmọ ìkẹhín àwọn ọmọ méje ti àwọn òbi rẹ...
sola asedeko ṣọlá asedeko jẹ́ òṣèré fiimu tí ìlu nàìjíríà àti olùdarí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi àbẹ̀ní fún ipa asíwáju rẹ̀ nínu àbẹ̀ní fiimu nàìjíríà kan ti ọdún 2006 tí túndé kèlání ṣe ìtọ́sọ́nà rẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí asedeko ní ìpínlẹ̀ èkó orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ka ìwé mẹ́wa rẹ̀ ní somori comprehensive high school ní ogb...
halima atete nigerian actress halima yusuf atete tí a tún mọ̀ ní halima atetetí a bí ní ọjọ́ 26 oṣù kọ́kànlá ọdún 1988 jẹ́ òṣèré fiimu nàìjíríà àti agbéré-jáde tí a bí tó sì dàgbà ní ìlu maiduguri ìpínlẹ̀ borno halima atete gbajúmọ̀ ní sinimá kannywood fún ipa tí ó ma n sáábà kó nígbà gbogbo bíi aláìṣedédé àti olójòwú ...
theresa edem theresa edem isemin ti a bi ni theresa edem jẹ oṣere ti o ni ẹbun naijiria n oṣere ti o mọ julọ fun awọn ipa rẹ ni ayamma music in the forest hotel majestic ati tinsel o wa si ọlá ni 2013 lẹhin iṣẹ rẹ ni “after the proposal” o pari ni ile-ẹkọ giga ọba awọn ọna igbesi aye ati eko a bi theresa ni uyo ipinle ...
deyemi okanlawon déyẹmí ọ̀kánlàwọ́n jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré onípele ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ gidi up tí wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ lórí ẹrọ amóhù-máwòrán ò tún kópa nínú eré an african city if tomorrow comes àti eré road to yesterday ó tún kóp...
belinda effah nigerian actress and presenter belinda effah ti a bi ni oṣu kejila ọjọ kẹrinla ọdun 1989 jẹ oṣere ati olukọni ti orilẹ-ede naijiria kan o gba aami eye oni ileri pupọ julọ ti ìṣirò ti odun ẹbun eye ni elekẹsan awọn ẹbun ile-ẹkọ afirika igbesi aye ati eko a bi effah ni oṣu kejila ọjọ kẹrinla ọdun 1989 ni ip...
linda ejiofor nigerian actress and model linda ejiofor ti a bi ni linda ihuoma ejiofor 17 oṣu keje 1986 jẹ oṣere ara ilu naijiria ati awoṣe lati ipinlẹ abia ti a mọ fun ipa rẹ bi bimpe adekoya ni m-net's ere telefisonu eleka tinsel a ti yan fun oṣere ti o dara julọ ni ipa atilẹyin kan ni ami ayeye elekesan ere afirika ...
joseph benjamin joseph benjamin jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé model olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ́lú àjọ mtn pẹ̀lú bí ó ṣe wà lára àwọn olùfilọ́ọ́lẹ̀ ètò ati fíforin dáni lára yá mtn project fame fún àwọn ọ̀dọ́ ó ti kópa nínú àwọn eré bíi tango with me mr and mrs...
john okafo john ikechukwu okafor tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí mr ibu jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré sinimá àti aláwàdà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà okafor jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré apanilẹ́rín ilẹ̀ nàìjíríà tí ó múṣẹ́ rẹ̀ lọ́kùnkúndùn tí ìṣe rẹ̀ sì ma ń kún fún ìwà òmùgọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ okafor jẹ́ ọmọ bíbí ì...
judith audu nigerian actress judith emike audu-foght tí a mọ̀ nídi iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi judith audu jẹ́ òṣèré fiimu ará nàìjíríà afẹwàṣiṣẹ́ àti olùgbéré-jáde ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi mofẹ́ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí nàìjíríà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ emerald pẹ̀lú àjọṣepọ̀ joseph benjamin carol king lilian esoro àti fẹ́...
ime bishop umoh ime bishop tí wọ́n tún pè níokon lagos tàbí udo yes jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé aláwàdà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà nigeria ìbẹ̀ré ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ ime jẹ́ ọmọ bíbí agbègbè nsit ibom àti ẹ̀yà ìbíòbíó láti ìpínlẹ̀ akwa ibom ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ yunifásitì uyo níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ philosophy ó ti bẹ̀rẹ...
lilian esoro lilian esoro tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 1982 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n yàn án fún ipò òṣèrébìnrin aláwàdà tó peregedé jùlọ nínú amì-ẹ̀yẹ ti '2013 africa magic viewers choice awards' ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ esoro kẹ́kọ́ jáde nípa ìmọ̀ ìṣèlú ní yunifásitì ti àb...
rachel bakam rachel bakam jẹ́ òṣèré ará orílẹ̀-èdè nàìjíríà ònkọ̀wé olóòtú ètò ori tẹlifíṣọ̀nù àti alátakò gbígbé ènìyàn fi ṣiṣẹ́ òun ni alákòso àti adarí rayzeds media ltd olùdásílẹ̀ ati alákòso tí nigerian water ski and wakeboard federation nwwf àti alámọ̀ràn fún performing musician employers association pman pẹ̀lú a...
anna banner nigerian pageant and actress anna ebiere banner tí a bí ní 18 oṣù keèjì 1995 jẹ́ olúborí ìdíje ẹ́wà at̀i òṣèré ní ọdún 2013 wọ́n de ládé ọmọbìnrin tó rẹwà jùlọ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì ṣojú nàìjíríà níbi ìdíje ẹ́wà àgbáyé ní ọduń 2013 bákan náà ó rí yíyán fún ipò olùrànlọ́wọ́ pàtàkì sí gomina henry dicks...
ebbe bassey nigerian american actress ebbe bassey jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ati amẹ́ríkà tí a yàn fún àmì-ẹ̀yẹ africa movie academy award kan fún tí òṣèré tí ó dára jùlọ ní ipa àtìlẹyìn nípasẹ̀ ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bi maa dede nínu ties that bind ní ọdún 2011 iṣẹ́-ìṣe bassey ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ilẹ...
liz benson elizabeth benson tí a bí ní oṣù kẹẹ̀rin ọjọ́ 5 ọdún 1966 jẹ́ òṣèré ará orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì tún jẹ́ onínúrere ẹ̀dá ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ rẹ̀ benson bẹ̀rẹ iṣẹ́ òṣèré ṣíṣe nígbàtí ó wà lọ́mọdé lọ́mọ ọdún márùn-ún iṣẹ́-ìṣe rẹ̀ àṣeyọrí rẹ̀ àti fífi iṣẹ́ fiimu sílẹ̀ benson di gbajúmọ̀ òṣèré nígbàtí ó ṣe ìfihàn...
caroline chikezie british actress caroline chikezie jẹ́ òṣèré ará orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti bírítìṣì tó gbajúmọ̀ fún kíkó àwọn ipa bíi sasha williams nínu eré as if elaine hardy nínu eré footballers' wives àti ipa cyberwoman nínu torchwood ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí chikezie ní england sí àwọn òbí ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ...
khanyi mbau kanyisile mbaubíi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù kẹwàá ọdún 1986 jẹ́ òṣèré àti atọkun ètò lórí tẹlẹfíṣọ̀nù ni orílẹ̀ èdè south áfríkà mbau di gbajúmọ̀ nítorí ipa doobsie tí ó kó nínú eré muvhango ni ọdún 2004 ó ṣe atọkun fun ètò the scoop ati the big secret ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí khanyasile ni ọdún 1995 ìyá ...
hlubi mboya hlubi mboya bíi ni ọjọ́ kẹji oṣù kẹta ọdún 1978 je òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó kọ ipa nandipha sithole nínú eré isindigo ó sì farahàn nínú eré dora's peace ni ọdún 2016 èyí sì lọ je ko gba àmì ẹ̀yẹ best supporting actress láti ọ̀dọ̀ safta award ó gbà àmì ẹ̀yẹ best supporting actress láti ọ̀dọ̀ golden...
denise zimba denise zimba bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 1988 jẹ́ òṣèré olórin oníjó àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ èdè south africa tí ó gbajúmọ̀ fún ipá mary gumede tí ó kó nínú eré generations the legacy ó darapọ̀ mọ́ eto v-entertainment ni ọdún 2013
boity thulo boitumelo thulo bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1990 tí orúkọ inagi rẹ jẹ boity jẹ́ òṣèré olórin oníṣòwò àti mọ́dẹ́lì lórílẹ̀ èdè south áfríkà ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí thulo sì ìlú potchefstroom ìyá mama rẹ sì ló tọ dàgbà òun nìkan ni ọmọ ìyá rẹ bí ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí monyash universit...
thando thabethe thando thabethe bíi ni ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 1990 jẹ́ òṣèré dj agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati àmbásẹ́dọ̀ àkókò láti ilẹ̀ áfríkà fún nivea ó ṣe atọkun fun ètò thando bares all lórí channel tlc ó kọ ipa nolwazi buzo nínú eré generations the legacy láti ọdún 2014 di ọdún 2017 ó jẹ́ dj lórí rádíiò fún 5fm ó ...
lota chukwu ugwu lotachukwu jacinta obianuju amelia jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí lota chukwu ó di gbajúmọ̀ òṣèré lẹ́hìn kíkópa rẹ̀ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ jenifa's diary ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú fúnké akíndélé juliana olayode àti falz níbi tí ó ti kó ipa gẹ́gẹ́ bi kik...
sylvaine strike sylvaine strike jẹ́ òṣèré akọ̀wé àti adarí eré orí ìtàgé lórílẹ̀ èdè south áfríkà ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí sì ìlú pretoria ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of cape town ó sì gboyè nínú ìmò dírámà ni ọdún 1993 iṣẹ́ strike jẹ́ adarí fún àwọn òṣèré ni ilẹ̀ iṣẹ́ fortune cookie theater ó jẹ́ ìkan l...
shoki sebotsane shoki sebotsane bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹjọ ọdún 1977 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó gbajúmọ̀ fún ipá celia kunutu tí ó kó nínú eré skeem saam ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ prudebs secondary school kí ó tó tesiwaju sì ilé ẹ̀kọ́ gíga tí tampere university of technology wọn yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré to dára jù l...
stephanie sandows stephanie ndlovu bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1991 jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré scandal àti shuga ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of johannesburg ó jẹ́ ìkan láàrin àwọn atọkun ètò ọmọdé tí àkòrí rẹ jẹ craz-e ó ṣe atọ...
manaka ranaka manaka ranaka bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 1979 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré generations the legacy ó kó ipa nandipha sithole nínú eré isindigo ní ọdún 2007 ó gbà ẹ̀bùn òṣèré tó dára jù lọ nínú ẹ̀fẹ̀ láti ọ̀dọ̀ south african film and television award ó lọ ...
antoinette pienaar antoinette pienaar bíi ni ọdún 1961 jẹ́ olórin akọ̀wé àti òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of stellenbosch níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò díráma ó gbajúmọ̀ fún ìtàn ìgbésí ayé àwọn èèyàn akíkanjú ni orílẹ̀ adúláwò tí ó má ń sọ ó jẹ́ ọmọ iṣẹ́ fún joannes willemse láti...
clarion chukwura chief clarion chukwura tí orúkọ ìbí rẹ̀ jẹ́ clara nneka olúwatóyìn foláshadé chukwurah 24 oṣù keèje ọdún 1964 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti olùfẹ́raǹ ọmọènìyàn iṣẹ́ ìṣe àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó ka ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ìlú èkó sááju kí ó tó lépa ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní queen of the rosary college ...
celeste ntuli celeste ntuli bíi ni kẹẹdọgbọn oṣù kẹjọ ọdún 1978 jẹ́ òṣèré àti aláwàdà ní orílẹ̀ èdè south áfríkà ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí olòrì fún ẹ̀fẹ̀ ni ilẹ̀ zulu wọ́n bíi ntuli ni ìlú empangeni níbi ó ti gba ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀ òun ni ọmọ kẹfà láàrín àwọn ọmọ mẹjọ tí àwọn òbí rẹ bí ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí durba...
zola nombona zola nombona bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 1992 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá shado tí ó kó nínú eré intersexions ni ọdún 2013 ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ victoria girl's high school no ìlú grahamstown kí ó tó wà lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí wits university níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò drama...
liz da-silva elizabeth ọmọ́wùnmí tekovi da-silva tí a bí ní oṣù kẹẹ̀fà ọjọ́ 10 ọdún 1978 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti tógò tí ó maá n sábà kópa ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà nínu fíìmù yorùbá ti nàìjíríà ní ọdún 2016 wọ́n yan da-silva fún àmì ẹ̀yẹ city people movie award fún ti òṣèré amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ tó dára jùlọ ẹ̀ka ti ...
yul edochie 'yul edochie ti a bi ni yul chibuike daniel edochie ọjọ keje oṣu kini ọdun 1982jẹ oṣere ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríàòun sì ni a darukọ lẹyin olokiki oṣere ara ilu russia yul brynner o wa lati ipinle anambra nàìjíríà ọmọ oṣere nàìjíríà pete edochie o dagba ni ilu eko ati enugu oun ni o kẹyin ninu awọn ọmọ mefa o ...
slindile nodangala slindile nodangala bíi ni ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹfà ọdún 1972 jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá ruby dikobe tí ó kó nínú eré generations nodangala dàgbà sí ìlú durban ìyá bàbà rẹ̀ ló sì tọju rẹ̀ nodangala tí bí ọmọ méjì iṣẹ́ nodangala ṣiṣẹ́ pẹ̀lú lyceum theater ni ìlú london ...
vatiswa ndara vatiswa ndara bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1970 jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orílẹ̀ èdè south áfríkà wọn bí sì ìlú mthatha ni ilẹ̀ eastern cape ní ọdún 1994 ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníróyìn ni orí rádíiò transkei ó ti ṣiṣẹ́ pẹlu awọn ilé iṣẹ́ rádíiò bíi radio bob kaya fm metro fm 5fm à...
lesego motsepe lesego motsepe bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1975 jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè south áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá letti matabane tí ó kó nínú eré isindigo láti ọdún 1998 títí di ọdún 2008 ó jáde láti sọ̀rọ̀ ní ọdún 2011 pé òhun ní àrùn kogboogun hiv o dàgbà sì ìlú meadowlands ó sì lọ sí...
tumi morake tumi morake bíi ni ọjọ́ kẹjìlélógún oṣù kejìlá ọdún 1081 jẹ́ òṣèré agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati akọ̀wé ni orílẹ̀ èdè south áfríkà ní ọdún 2018 ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní ilé áfríkà tí ó má gbé eré ẹ̀fẹ̀ rẹ sì orí netflix òun sì obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ma ṣe atọkun fun ètò comedy central presents ni ilẹ̀ áfríkà ó lọ sí il...
uche elendu nigerian actress singer and entrepreneur uche elenduti a bi ni ọjọ kẹrinla oṣu keje odun 1986 jẹ oṣere ara ilu naijiria ati akorin ati otajaa ṣe apejuwe rẹ gẹgẹbi ọkan ninu awọn oju ti o ṣe deede julọ ni ile-iṣẹ fiimu ti naijiria lati akọkọ ti o wa ni ọdun 2001 titi di ọdun 2010 nigbati o gba isinmi lati il...
omowumi dada ọmọ́wùmí dàda jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi folákẹ́ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù ti m-net kan jemeji ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó kópa nínu fíìmù èdè yorùbá kan somewhere in the dark ní ọdún 2017 èyítí ó gba àmì ẹ̀yẹ ti fíìmù abínibí tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ amvca awards ti ọdún ...
julius agwu julius agwu bí ni oṣù kejè oṣù igbe ọdún 1973jẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín òṣèré olórin àti atọ́kùn òun ni aláṣẹ àti olùdarí iléeṣẹ́ reellaif limited music and movie production company ó tún jẹ́ olùdámọ̀ràn lórí amúlùúdùn àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ ajẹmọ́-ìṣípayá òun ni olótùú àwọn eré bíi adárìínpani crack ya cribs laff 4 chris...
jemima osunde jemima osunde tí wọ́n bí ní ọgbọ̀njọ́ oṣù kẹrin ọdún 1996 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé model àti olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán ọmo orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di ìlú-mòọ́ká lẹ́yìn tí í ó kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn jemima nínú eré àtìgbà-dégbà onípele ti shugawọ́n yan osunde fún amì-ẹ̀yẹ ti best actress in a leading r...
jennifer eliogu nigerian actress and singer ' 'jennifer eliogu' 'ti a bi ni oṣu kẹrin ọjọ ọgbọn ọdun 1976 jẹ oṣere ati olorin ilu naijiria kan o kun akiyesi fun jije oṣere ni ọdun 2016 eliogu gba ‘‘ ami idanimọ pataki ’’ ni ami idanilaraya ilu eniyan fun awọn ẹbun rẹ si ile-iṣẹ fiimu ti naijiria eliogu ni ọdun 2014 fun...
stella damasus stella damasus tí a bí ní oṣù kẹẹ̀rin ọjọ́ 24 ọdún 1978 jẹ́ òṣèré àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti rí yíyàn fún òṣèré tí ó dára jùlọ ní ipa aṣáájú níbi ayẹyẹ africa movie academy awards ní ọdún 2009 ó gba àmì ẹ̀ye fún ti òṣèré tó dára jùlọ níbi ayẹyẹ nigeria entertainment awards ní ọdún 2007 bákan...
odunlade adekola nigerian actor odunlade adekola ti a bi ni ọjọ okanleọgbọn oṣù kejìlá odun 1976 je osere ni ilu naijiria akorin oluṣe fiimu ati oludari won bi ni abeokuta o si dagba ni abeokuta ipinle ogun ṣugbọn omo-ilu otun ekiti ni ipinle ekiti ni o gbaye-gbale pẹlu ipo adari rẹ ninu fiimu 2003 ti ishola durojaye a...
samke makhoba south african actress samkelisiwe samke makhoba tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n ọdún 1989 jẹ́ òṣèré gusu afirika tí ó kópa nínú eré shuga èyí tí mtv gbé kalẹ̀ ìgbésí ayé wọ́n bí makhoba sí ìlú umlazi ní ọdún 1989 ó kọ́kọ́ yàn láti kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ science ní ilé- ẹ̀kọ́ gíga ti university of western cape ṣùgbọ́...
caroline danjuma caroline danjuma tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ bi caroline ekanem jẹ́ òṣèré ọmọ nàìjíríà kan ó ṣe ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ lóju amóhù-máwòran ní ọdún 2004 níbi tí ó ti kópa nínu àwọn gbajúmọ̀ fíìmù kan láti ọwọ́ chico ejiro lẹ́hìn fífi iṣẹ́ fíìmù sílẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ ó ṣe ìpadàbọ̀ ní ọdún 2016 tí ó sì kópa nínu eré afìfẹ...
awa traoré awa traoré èdè lárúbáwá أوا تراوري jẹ́ òṣèré fíímù àti onkọ̀wé ní ìlú ḿalì iṣẹ́ traoré bẹ̀rẹ̀ eré síse rẹ̀ pẹ̀lú fíímù l'enfant noir ní ọdún1995 lẹ́hìnńà ó ṣiṣẹ́ bí ọdẹ ní fíímù ránpẹ́ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ denko èyí tí mohamed camara se adarí rẹ̀ ní ọdún 1993 fíímù náà gba ìyìn pàtàkì àti àmì ẹ̀yẹ grand prix ní...
michelle dede michelle dede jẹ́ atọ́kùn ètò orí tẹlifíṣọ̀nù nàìjíríà àti òṣèré ó ṣe àjọgbéjáde fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ flower girl ó sì tún kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù alátìgbà-dègbà kan desperate housewives africa àti fíìmù aṣaragágá tí ọduń 2017 what lies within ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí dede ní orílẹ̀-èdè j...
ini dima-okojie ini dima-okojie ọjọ́ ìbí ni 24 june 1990 jẹ́ òṣèré tí wá ní orílé èdè nàìjíríà ó fi iṣé rẹ silẹ ní investment banking láti fí orúkọ sílẹ̀ ní newyork film academy ó kọ́kọ́ yóò jáde nínú eré taste of love lẹyìn ní ò bèrè sí ní jáde nínú àwọn eré kàn kàn bi multiculturalromcom namaste wahala ni 2012 àti er...
àlàdé arómirẹ́ muyideen agboọlá àlàdé arómirẹ́ tí gbogbo ènìyàn tún mọ̀ sí àlàdé arómirẹ́ tí wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ èkó ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹjọ ọdún 1963 jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré ìtàgé agbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ àlàdé lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ansar-ud-deen tí ó wà ní alakoso ní ìpí...
iretiola doyle ìrètíọlá doyle tí orúkọ ìbí jẹ́ ìrètíọlá olúṣọlá àyìnkẹ́ jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí doyle ní ọjọ́ 3 oṣù karùn-ún ọdún 1967 ní ìpínlẹ̀ òndó ṣùgbọ́n ó lo àwọn ìgbà èwe rẹ̀ pẹ̀lú ẹbí rẹ̀ ní boston orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà lẹ́hìn tí ó padà sí nàìjíríà ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ...
amanda ebeye amanda mike-ebeye tí a bí ní 30 oṣù kẹẹ̀rin ọdún 1986 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti afẹwàṣiṣẹ́ ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu eré clinic matters àti super story iṣẹ́ ìṣe ó ṣe ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ nínu fíìmù níbi eré weeping tiger 2008 nínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan ti 2013 èyí tí information nigeria...
uche ogbodo uche ogbodo tí a bí ní oṣù kaàrún ọjọ́ 17 ọdún 1986 jẹ́ òṣèré fíìmù àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí ogbodo ní ìpínlẹ̀ enúgu ìrìn-àjò ogbodo sí nollywood bẹ̀rẹ̀ lẹ́hìn ìpinnu bàbá rẹ̀ láti forúkọ rẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ actors guild of nigeria ní ìpínlẹ̀ enúgu láti ìgbà eré àkọ́kọ...
bolaji ogunmola bọ́lájí ògúnmọ́lá jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ ògúnmọ́lá ní ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní philomena nursery and primary school èbúté métta ṣááju kí ó tó lọ sí ìlú ìbàdàn fún ètò ẹ̀kọ́ mẹ́wàá rẹ̀ ó kẹ́ẹ̀kọ́ ìṣàkóso ìṣòwò ní national open university of nigeria ògúnmọ́lá tún jẹ...
ifeanyi kalu ifeanyi kalu jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé model àti aránṣọ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ lagod cougars òun àti uche jombo monalisa chinda àti alex ekubo ni wọ́n jọ kópa nínú eré náà ó tún kópa nínú eré onípele àtìgbà-dégbà kan tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní ...
daniella okeke daniella okeke jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2013 ó kó ipa jọké nínu eré lagos cougars ipa kan tí ó fun lánfàní yíyàn fún ti òṣère tí ó dára jùlọ ní ipa asíwájú níbi ìkéde ẹ̀lẹ́kẹẹ̀wá ti african movie academy awards àti nigeria entertainment awards ti ọdún 2014 ìgbé ayé rẹ̀ okeke ni a bí ní o...
stephanie okereke linus stephanie linus stephanie onyekachi okereke 2 oṣù kẹẹ̀wá 1982 jẹ́ òṣèré olùdarí eré àti afẹwàṣiṣẹ́ ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti àwọn yíyàn fún iṣẹ́ rẹ̀ bí òṣèré tó fi mọ́ àmì-ẹ̀yẹ ti reel ti ọdún 2003 fún òṣèré tí ó dára jùlọ àmì-ẹ̀yẹ afro hollywood ti ọdún 2006 fún òṣèré tí ó dára jùlọ...