raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
neptune |
mẹ́kíúrì planẹti |
sístẹ̀mù òrùn |
mársì mársì jẹ́ ìsọ̀gbé oòrùn kẹrin lati oòrùn tí ó sì jẹ́ ìkejì ìsọgbé tí ó kéré jù lẹ́yìn mercury nínú ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po wón sọọ́ lórúkọ roman god of war wọ́n ma ń sábà pèé ní ìsọ̀gbé oòrùn pupa nítori àyè tí iron oxide gbà lóju rẹ̀ jẹ́ kó ní ìrísí pupa |
sátúrnù sátúrnù ni is the sixth planeti kefa si orun ati planeti keji totobijulo ninu sistemu orun leyin jupiteri |
úránù úránù ni planeti keje si orun |
nẹ́ptúnù nẹ́ptúnù ni kejo ti eyi tojinajulo si orun ninu sistemu orun |
òòrùn |
edward gibbon edward gibbon tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1737 april 27 1737 january 16 1794 jẹ́ ònkọ̀wé àti olóṣèlú ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì |
fouad mebazaa fouad mebazaâ lárúbáwá ojoibi 16 june 1933 je oloselu omo ile tunisia to di je adipo aare ile tunisia lati 15 january 2011 |
age of the earth |
ọjọ́orí ayé ọjọ́orí ayé ti je sisepinnu pe o je 454 billion odun 454 × 109 odun ± 1 ojoori yi duro lori eri lati inu isojoori radiometriki awon eroja meteoriti be sini o ni bamu mo awon ojoori awon samples atijojulo ti a mo lori aye ati ninu osupa |
radioactive decay |
owl |
chromium trioxide |
triọ́ksídì krómíọ̀mù triọ́ksídì krómíọ̀mù tabi krómíọ̀mù ọlọ́ksíjìnmẹ́ta chromium trioxide je adapo ainiorgani to ni fomula cro3 |
alcohol |
ọtí ninu kemistri ọtí alcohol je adapo elemin yiowu nibi ti adipo onimusise hydroxyl kan -oh je sisopo mo atomu karbon kan |
benjamin franklin benjamin franklin january 17 1706 april 17 1790 je oloselu ati ikan ninu awon baba oludasile orile-ede amerika |
zhao ziyang zhao ziyang pronounced 17 october 1919 17 january 2005 je oloselu onipo giga ni saina prc ohun ni he was the olori ijoba ile saina keta lati 1980 de 1987 ati akowe agba egbe komunisti ile saina lati 1987 de 1989 |
goma goma jẹ́ ìlú ní apá ìlà-orùn orílẹ̀-èdè kongo |
montesquieu |
antoine césar becquerel antoine césar becquerel march 7 1788 january 18 1878 je onimo sayensi ara fransi ati asiwaju ninu eko isele onina ati yindinyindin luminescent phenomena |
sierra leone civil war |
ogun abẹ́lé siẹrra lẹ́ónè the sierra leone civil war bere ni 23 march 1991 nigbati revolutionary united front ruf pelu itileyin latowo awon ajagun pataki national patriotic front of liberia npfl ti charles taylor fe fi tipatipa lejoseph momoh to je aare orile-ede sierra leone kuro lori ijoba eyi fa ogun to pa awon eniy... |
james watt james watt frs frse 19 january 1736 25 august 1819 je omo skotlandi adasile ati onimo iseero elero |
sheep |
àgùtàn àwọn àgùtàn ovis aries jẹ́ àwọn ẹranko afọ́mọlọ̀mú tí wọ́n sì ma ń tún ónjẹ wọn pọ̀ jẹ lẹ́yìn tí wọ́n bá ti jẹun tán bákan náà ni wọ́n sì tún jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin tí wọ́n ma ń jẹ̀ kiri ẹ̀wẹ̀ wọ́n tún jẹ́ ẹran ọ̀sìn abẹ́lé |
ovis aries |
john h johnson john harold johnson january 19 1918 august 8 2005 je onisowo ati atewejade ara amerika |
esteban echeverría josé esteban antonio echeverría september 2 1805 january 19 1851 je olukowe ati akoewi ara argentina |
pierre-joseph proudhon pierre-joseph proudhon 15 january 1809 in besançon 19 january 1865 ni passy je oloselu amoye alajojeanfani ati sosialisti ara fransi |
new horizons new horizons ni iranlose oko-ofurufu oniroboti ti nasa to unlo lowolowo si planeti arara pluto |
plùtò plùtò oruko 134340 plùtò aami tabi ni planeti arara to ni akojojulo keji ninu sistemu orun leyin eris ati isupo agbarajo kewa to je sisakiyesi pe ohun lo lojuonaiyipo taara òrùn |
mahamane ousmane mahamane ousmane ojoibi january 20 1950 je oloselu ara niger ohun ni aare adiboyan akoko ati ikerin ile nijer lati 16 april 1993 titi igba ti o je lole kuro pelu ifipagbajoba ologun ni 27 january 1996 |
tandja mamadou |
amilcar cabral amílcar lopes da costa cabral 1924--12 1924 1973--20 1973 jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ iṣẹ́-àgbẹ̀ olùkọwé marksistì agbógunti ìmúnisìn àti olóṣèlú ará guinea-bissau |
garrincha manuel francisco dos santos october 28 1933 january 20 1983 to gbajumo pelu oruko alaje garrincha little bird je agbaboolu-elese ni ipo arin egbe otun ati iwaju ara brazil to ran egbe agbaboolu brazil lowo lati gba ife eye agbaye ni 1958 ati 1962 |
khan abdul ghaffar khan khan abdul ghaffar khan 1890 - 20 january 1988 pashto خاں عبدالغفار خاں híndì was a pashtun political and spiritual leader known for his non-violent opposition to british rule in india a lifelong pacifist a devout muslim and a close friend of mahatma gandhi he was also known as badshah khan also... |
prussia prussia latin borussia prutenia pólándì old prussian prūsa |
billy ocean billy ocean ojoibi leslie sebastian charles 21 january 1950 je omo trinidad ara ilegeesi to gba ebun grammy to je olorin pop ati rhythm and blues international pop hits in the 1970s and 1980s he was the main british-based rb singer / songwriter of the 1980s |
manuel francisco dos santos |
gold coast gold coast le jẹ́ |
sam cooke samuel cook january 22 1931 december 11 1964 to gbajumo bi sam cooke je akorin gospel rb soul ati pop ara amerika akorin ati onisowo o je gbigba bi ikan ninu awon asiwaju ati oludasile orin soul wo unpe bi oba orin soul fun iru ohun ikorin re ati ipa to ni lori orin agbaye odeoni ipa re lori orin soul lo fa i... |
francis bacon francis bacon 1st viscount saint alban kc 22 january 1561 9 april 1626 je amoye agbaalu onimo sayensi agbejoro adajo ati olukowe ara ilegeesi |
thomas samuel kuhn |
lord byron george gordon byron 6th baron byron later george gordon noel 6th baron byron frs 22 january 1788 19 april 1824 to gbajumo bi lord byron iba bairon je akoewi ara britani ati eni asiwaju ninu iseromansi ninu awon iwe byron to gbajumo julo ni she walks in beauty when we two parted ati so we'll go no more a rovi... |
camille jordan marie ennemond camille jordan january 5 1838 january 22 1922 je onimo mathimatiki ara fransi to gbajumo fun ise ipilese re lori ero adipo ati eko cours d'analyse re |
telly savalas aristotelis telly savalas january 21 1922 january 22 1994 je osere ati akorin filmu ati telifisan ara amerika ti o sise fun bi ogoji odun |
giambattista vico giovanni battista giambattista vico tabi vigo 23 june 1668 23 january 1744 je amoye oloselu asoro akoitan ati agbejoda ara italia |
pierre bourdieu pierre bourdieu 1 august 1930 23 january 2002 je onimo oro-awujo onimo oro-omoniyan ati amoye ara fransi |
casablanca casablanca arabic الدار البيضاء ad-dār al-bayḍāʼ oruko ni ede amazigh anfa / je ilu ni apa iwoorun morocco leba okun atlantiki ibe na tun ni oluilu agbegbe grand casablanca |
christian wolff christian wolff less correctly wolf bakanna bi wolfius eleye bi christian freiherr von wolff 24 january 1679 - 9 april 1754 je amoye ara germany |
edith wharton edith wharton oruko abiso edith newbold jones january 24 1862 august 11 1937 je eni to gba ebun pulitzer-winning american onitan olukowe itan soki ati aran aso-oge ara amerika |
rafael caldera rafael antonio caldera rodríguez 24 january 1916 24 december 2009 lo je aare ile venezuela lati 1969 de 1974 ati lati 1994 de 1999 |
homi j bhabha homi jehangir bhabha' frs 30 october 1909 24 january 1966 je onimo fisiksi ara india |
thurgood marshall thurgood marshall july 2 1908 january 24 1993 je agbaejoda ara amerika ati omo afrika amerika akoko ni ile-ejo gigajulo ile amerika |
4 nọ́mbà ẹrin 4 jẹ́ nọ́mbà iye ati glyph tó dúró fún nọ́mbà náà ó jẹ́ nọ́mbà àdábáyé tó tẹ̀lé ẹta 3 sùgbọ́n tó síwájú aárùn-ún 5 |
5 nọ́mbà aárùn 5 jẹ́ nọ́mbà iye ati glyph tó dúró fún nọ́mbà náà ó jẹ́ nọ́mbà àdábáyé tó tẹ̀lé ẹrin 3 sùgbọ́n tó síwájú ẹfa 6 |
winter olympic games |
eusébio eusébio da silva ferreira born 25 january 1942 commonly known simply as eusébio is a retired portuguese football forward he is considered one of the best footballers of all-time by the iffhs he helped the portuguese national team reach third place at the 1966 world cup being the top goalscorer of the tournament... |
robert boyle robert boyle frs 25 january 1627 31 december 1691 je ara orundun 17k amoye aladanida asekenistri asefisiksi ati oluda to tun gbajumo fun iwe re lori oro-olorun o lokiki fun ofin boyle |
etta james etta james oruko abiso jamesetta hawkins oṣù kínní 25 1938 - oṣù kínní 20 2012 je akorin blues soul rb rock roll gospel ati jazz ara amerika eni to bere ise orin kiko larin ewadun 1950 o gbajumo pelu orin bi dance with me henry at last tell mama ati i'd rather go blind awon eyi to ko fun ra re o koju orisiri... |
al capone alphonse gabriel al capone january 17 1899 january 25 1947 je odaran ati gangster omo italia amerika |
stephen cole kleene stephen cole kleene january 5 1909 hartford connecticut united states january 25 1994 madison wisconsin je amomathimatiki ara amerika to seranlowo lati sefilole fun sayensi komputa oniriro |
manuel lopes manuel antónio de sousa lopes december 23 1907 in mindelo - january 25 2005 je omo orile-ede cape verde olukowe alaroko ati oludasile litireso odeoni cape verde |
haute-savoie haute-savoie arpitan savouè d’amont / hiôta-savouè je ikan ninu awon apaipin ile fransi won unpe ni haute to tumosi giga ni faranse nitoripe o budo sinu awon oke alps |
àwọn ìdíje òlímpíkì ìgbà otútù àwọn ìdíje òlímpíkì ìgbà otútù ni awon idije orisirisi ere-idaraya to waye ni odoodun merin o koko waye ni 1924 ni fransi àtòjọ àwọn ìdíje note unlike the summer olympics the cancelled 1940 winter olympics and 1944 winter olympics are not included in the official roman numeral counts for ... |
concepción chile concepción je ilu kan ni tsile oluilu igberiko concepción ati fun agbegbe biobio tabi agbegbe 8k concepción ninla gran concepción nika kun talcahuano san pedro de la paz hualpén chiguayante penco tomé lota coronel hualqui ati concepción je agbegbe keji totbijulo ni tsile pelu awon olugbe 889725 ikaaral... |
gamel abdel nasser |
gnassingbe eyadema |
charles de gaulle |
phillip nnaemeka-agu phillip nnaemeka-agu february 28 1928 - january 24 2011 je onidajo ara naijiria |
léopold ii of belgium |
leopold 2k ilẹ̀ bẹ́ljíọ̀m leopold 2k duki 9 april 1835 17 december 1909 lo je oba awon ara beljiom keji won bi ni brussels gege bi omokunrin keji leopold 1k ati louise-marie of orléans o joba leyin baba re ni 17 december 1865 titi di ojo iku re |
leopold ii of belgium |
united arab republic |
orílẹ̀-èdè olómìnira aṣọ̀kan árábù the united arab republic lárúbáwá arabic pronunciation al-jumhuriyah al-arabiyah al-muttahidah international arabic pronunciation al-jumhuriyah al-arabiyah al-muttahidah often abbreviated as the uar was a union between egypt and syria the union began in 1958 and existed until 1961 w... |
william cullen william cullen frs frse frcpe 15 april 1710 5 february 1790 je aseise-agbe oluwosan ati asekemistri ara skotlandi |
thomas carlyle thomas carlyle 4 december 1795 5 february 1881 je omo skot olukowe oniyeye alaroko akoweitan ati oluko ni igba aye fiktoria |
upper volta |
ọjọ́ 1 oṣù kejì |
ọjọ́ 2 oṣù kejì |
ọjọ́ 3 oṣù kejì |
ọjọ́ 4 oṣù kejì |
ọjọ́ 5 oṣù kejì |
ọjọ́ 6 oṣù kejì |
ọjọ́ 7 oṣù kejì |
ọjọ́ 8 oṣù kejì |
ọjọ́ 9 oṣù kejì |
ọjọ́ 10 oṣù kejì |
ọjọ́ 11 oṣù kejì |
ọjọ́ 12 oṣù kejì |
ọjọ́ 13 oṣù kejì |
ọjọ́ 14 oṣù kejì |
ọjọ́ 15 oṣù kejì |
ọjọ́ 16 oṣù kejì |
ọjọ́ 17 oṣù kejì |
ọjọ́ 18 oṣù kejì |
ọjọ́ 19 oṣù kejì |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.