raw_text
stringlengths
2
128k
ọjọ́ 20 oṣù kejì
ọjọ́ 21 oṣù kejì
ọjọ́ 22 oṣù kejì
ọjọ́ 23 oṣù kejì
ọjọ́ 24 oṣù kejì
ọjọ́ 25 oṣù kejì
ọjọ́ 26 oṣù kejì
ọjọ́ 27 oṣù kejì
ọjọ́ 28 oṣù kejì
ọjọ́ 29 oṣù kejì
1 oṣù kejì
2 oṣù kejì
3 oṣù kejì
4 oṣù kejì
5 oṣù kejì
6 oṣù kejì
7 oṣù kejì
8 oṣù kejì
9 oṣù kejì
10 oṣù kejì
11 oṣù kejì
12 oṣù kejì
13 oṣù kejì
14 oṣù kejì
15 oṣù kejì
16 oṣù kejì
17 oṣù kejì
18 oṣù kejì
20 oṣù kejì
21 oṣù kejì
22 oṣù kejì
23 oṣù kejì
24 oṣù kejì
25 oṣù kejì
26 oṣù kejì
27 oṣù kejì
28 oṣù kejì
29 oṣù kejì
ọjọ́ 1 oṣù kẹta
ọjọ́ 2 oṣù kẹta
ọjọ́ 3 oṣù kẹta
ọjọ́ 4 oṣù kẹta
ọjọ́ 5 oṣù kẹta
ọjọ́ 6 oṣù kẹta
ọjọ́ 7 oṣù kẹta
ọjọ́ 8 oṣù kẹta
ọjọ́ 9 oṣù kẹta
ọjọ́ 10 oṣù kẹta
ọjọ́ 11 oṣù kẹta
ọjọ́ 12 oṣù kẹta
ọjọ́ 13 oṣù kẹta
ọjọ́ 14 oṣù kẹta
ọjọ́ 15 oṣù kẹta
ọjọ́ 16 oṣù kẹta
ọjọ́ 17 oṣù kẹta
ọjọ́ 18 oṣù kẹta
ọjọ́ 19 oṣù kẹta
ọjọ́ 20 oṣù kẹta
ọjọ́ 21 oṣù kẹta
ọjọ́ 22 oṣù kẹta
ọjọ́ 23 oṣù kẹta
ọjọ́ 24 oṣù kẹta
ọjọ́ 25 oṣù kẹta
ọjọ́ 26 oṣù kẹta
ọjọ́ 27 oṣù kẹta
babatunde omidina babatunde omidina tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ bàba sùwé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1958 jẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ òṣèré aláwàdà ipa àwàdà ni ó sìn máa ń kó nínú sinimá tàbí eré orí ìtàgé tí ó bá ti kópa eré orí ẹ̀rọ tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ...
fẹ́mi adébáyọ̀ fẹ́mi adébáyọ̀ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1973 jẹ́ amòfin gbajúmọ̀ òṣèré olóòtú àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlọrin ni ìpínlẹ̀ kwara bákan náà fẹ́mi adébáyọ̀ títí di ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2019 jẹ́ olùdámọ̀ràn pàtàki lórí àṣà ìrìn-afẹ́ àti iṣẹ́-ọ̀nà fún gó...
iyán iyán jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ ilẹ̀ yorùbá tó gbajúmọ̀ jùlọ iṣu funfun ló dára jù fún iyán gúngún a lè fi iyán jẹ ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ ẹ̀gúsí tàbí ilá gbogbo ilẹ̀ yorùbá ni wọ́n tí máa ń jẹ iyán ṣùgbọ́n iyán jíjẹ wọ́pọ̀ jùlọ láàárín àwọn ìjẹ̀ṣà òndó àti èkìtì àwọn èròjà iyán gúngún iṣu ni ọba èròjà tí wọ́n máa ń fi gúnyán l...
godwin obaseki godwin nogheghase obaseki ọjọ́ ìbí 1 agẹmọ 1957 ní ilu benin nigeria jẹ́ olóṣèlú àti oníṣòwò kan ní ìlú naijiria to sì jẹ gómìnà ipinle edo àtọwò wọ́n gbé ìpò gómíná fun ní ọjó ìkejìla bèlu 2016 ní oun lo jẹ́ olóyè economic and strategy team látọwọ́ gómìnà ìṣáájú adams oshiomole ní òṣù erẹ́nà l ọdún 2009
sunday omobolanle sunday ọmọbọ́láńlé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí papi luwe ni wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1954 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà olóòtú oǹkọ̀tàn àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìyàwó rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò peju ogunmola bẹ́ẹ̀ náà ọmọkùnrin...
peju ogunmola peju ogunmola tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́ta jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin oǹkọ̀tàn olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí yorùbá láti orílẹ̀ èdè nàìjíríà bàbá rẹ̀ ni kọ́lá ògúnmọ́lá gbajúgbajà òṣèré tíátà tí ó ti di olóògbé ọkọ rẹ̀ ní òṣèré aláwàdà sinimá àgbéléwò sunday ọmọbọ́láńlé tí gbó ènìyàn mọ̀ ...
súnkànmí ọmọbọ́láńlé súnkànmí ọmọbọ́láńlé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1981 jẹ́ gbajúgbajà òṣèré àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú ìlọrà ni ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè nàìjíríà súnkànmí jẹ́ ọmọ bíbí inú gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí papi luwe ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ súnkànmí bẹ̀...
markaz agége markaz agége jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ẹ̀sin mùsùlùmí àti lárúbáwá tí ó fìdí kalẹ̀ sí ìlú agége ní ìpínlẹ̀ èkó wọ́n kọ́kọ́ dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sileẹ̀ ní ọdún 1952 ní ìlú abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn ṣáájú kí wọ́n gbe wá sí ìlú agége lábẹ́ àṣẹ olùdásílẹ̀ sílẹ̀ rẹ̀ olóògbé sheik adam abdulahi al-ilory ní ọdún 1954 ilé-ẹ̀kọ́ yí...
femi branch fẹ́mi babáfẹ́mi branch ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn ún ọdún 1970 14-5-1970 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé yorùbá àti gẹ̀ẹ́sìolùkọ̀tàn àti akọ ewì àpilẹ̀kọ adarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ibẹ́rẹ́ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí fẹ́mi ní ìlú ṣàgámù ní ìpínlẹ̀ ìpínlẹ̀ ògùn sínú ẹbí ọ̀ṣúnkọ̀yà ní ọdú...
wólíì àrólé wólíì àrólé eni tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ olúwatóyìn báyégùn ni wọ́n bí ní ìlú ìkàrẹ́-àkókó ní ìpínlẹ̀ òndó jẹ́ òṣèré orí ìtàgé àti adẹ́rínpòṣónú ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ olúwatóyìn lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ yi olápàdé àgòrò tí ó wà ní àpáta ní ìlú ìbàdàn tí ó si lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama government...
alángbá alángbá jẹ́ ọ̀kan lára ẹbí lángbá tí ẹ̀yà wọn tó 300 níye irúfẹ́ alángbá yí wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ éṣíà australia àti diẹ̀ ní agbègbè southern europe ọ̀pọ̀ nínú àwọn alángbá yí ni wọ́n ma ń pè dragon nítorí ìrísí wọn ó fara jọ ọ̀gà ṣùgbọ́n tí kìí yí àwọ̀ padà bí ọ̀gà ìwádìí sáyẹ́nsì fihàn pé ó tó oríṣi ẹgbẹ̀rú...
ìrun wítìrí ìrun wítìrí ninu ẹ̀sìn islam jẹ́ ẹ̀ka kán nínú àwọn èlé ìrun nafila ó jẹ́ ìrun kán tì a ma n kí ní alaalẹ́ lẹ́yìn ìrun ishai àtí pé ó jẹ́ ìrun ẹyọ̀ọ̀kan tí afí n parí ìrun ojúmọ́ lẹ́yìn shafuhi ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn suhhan tí ó pọn dandan tí àwọn onímọ̀ nínú ẹ̀sìn islam fọwọ́ sí ìrun wítìrí ni ó gbọ́dọ̀ kẹ́...
aláùsá ìkẹjà aláùsá jẹ́ àdúgbò tí ó gbòrò jùlọ ní àárín ìlú ìkẹjà ní ìpínlẹ̀ èkóibẹ̀ ni olú ilé-iṣẹ́ ìjọba àti ọ́físì gómìnà ìpínlẹ̀ èkó wà tí ó sì jẹ́ ibùjókòó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ní ìlú èkólára àwọn ilé-iṣẹ́ tó lààmì laaka tí ó f7ìdí kalẹ̀ sí aláùsá ni ilé-iṣẹ́ cadbury nigeria plc ibẹ̀ náà tún ni gbàgàn ìgbafẹ́ mko a...
ìpájà ìpájà jẹ́ ìlú kan tí ó kalẹ̀ sí ìlú èkó ní abẹ́ àṣẹ ìjọba ìbílẹ̀ alímọ̀ṣọ́ìlú náà tobi púpọ̀ tí ósì fi àyè gba ọ̀gọ̀rọ̀ ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbé yálà ọmọ ìlú tàbí ààrè oríṣiríṣi ilé ìgbafẹ́ àti ìtura ló wà ní ìlú náà pẹ̀lú
sányẹ̀rì ọláníyì mikail àfọ̀njá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí sányẹ̀rì jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé adẹ́rínpòṣónú olùgbéré jáde ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí oláníyì àfọ̀njá ní ìpìlẹ̀ ọ̀yọ́ tí ó si jẹ́ akọ́bí ẹbí rẹ̀ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ st micheal ní oke-ìbò àti ilé-ẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ girama durbar ní ìpínlẹ̀...
yinka quadri alhaji àkàní ọláyínká quadri tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kọkànl ọdún 1959 6-9-1959 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré jáde àti adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n bi tí ó sì dàgbà sí àdúgbò lagos island ní ìpínlẹ̀ èkó àmọ́ tí ọ́ jẹ́ baba àti ìyá rẹ̀ wá láti ìlú òró ní ìpínlẹ̀ kwara òun ni wọ́n fi jẹ oyè àgbà ...
fásitì anchor ifáfitì anchor jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tí aládàáni tí ó jẹ́ ti ìjọ deeper christian life ministry ilé-ẹ̀kọ́ náà wà ní agbègbè kan ní ìlú ayọ̀bọ́ ìpájà ní ìpínlẹ̀ èkóní orílẹ̀-èdè nàìjíríà =àwọn ìtọ́kasí==
ibojì òkú ibojì òkú tàbíitẹ̀ òkú jẹ́ ibi tí wọ́n ń sin àwọn ènìyàn tí ó ti kú tàbí papò dà sí wọ́n ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀-orúkọ yíibojì láti inú èdè gíríkì tí ó túmọ̀ sí ibùsùn tí ó túmọ̀ sí wípé ìwọ̀nba ilẹ̀ tí wọ́n yà sọ́tọ̀ yí ni wọ́n ṣàdáyanrí fún sín sin àwọn aláìsí sí wọ́n sábà ma ń lo àwọn gbólóhùn wọ̀nyí ibojì òkú tàbí it...
bayo omoboriowo bayo omoboriowo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 1978 jẹ́ ayawòrán-kọròyìn ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ayàwòrán àgbà fún ààrẹ orílẹ̀-èdè nàìjíríà lọ́wọ́́lọ́wọ́ muhammadu buhari ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ọmọ bíbí ìlú èkó ni báyọ̀ ọmọ́boríowó kódà muṣin ní ìlú èkó lo tí dàgbà báy...
enoch adébóyè nigerian clergyman pastor enoch adéjàré adébóyè ẹni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta oşù ęrénà ọdún 1942 jẹ́ òjíṣẹ̀ ọlọ́run ọmọ bíbí ifẹ̀wàrà ni ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni pásítọ̀-àgbà yànyàn ati olùdarí ìjọ oníràpadà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ìjọ ìràpadà ti krístì the redeemed christian chur...
bàtà bàtà jẹ́ ohun tí ọmọ ènìyàn ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti lè fi rìn ati láti se dáàbòbò ẹsẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìjàmbá tó lè ṣakóbá fún ẹsẹ̀ ìwúlò bàtà wọ́n ma ń lo bàtà yálà lásìkò ẹ̀rùn tàbí òjò wọ́n ń lo bàtà láti fi ṣe iṣẹ́ èyíkéyí ṣe eré ìdárayá ṣe ìdáàbòbò ara àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ láì ko sí bàtà láyé òde òní ó lè ṣòro fún ọm...
tescom ìpínlẹ̀ èkó tescom ìpínlẹ̀ èkó tí ó túnọ̀ sí teaching service commission jẹ́ àjọ tí ó ń rí sí ètò ìgbanisíṣẹ́ olùkọ́ ní ìpínlẹ̀ èkó ni ó ti fìgbà kan wà lábẹ́ ìṣàkóso post- primary teaching service commission pp- tescom pẹ̀lú oríṣiríṣi àwọn adarí láti ọdún 2004 ṣáájú kí wọ́n tó dá teachers’ establishment and pen...
ọdẹ ọdẹ ni orúkọ tí a ń pe àwọn àkàndá ènìyàn kan tí wọ́n yan iṣẹ́ pípa ẹranko ìgbẹ́ dídẹ odò pípa ẹyẹ oríṣiríṣi lọ́pọ̀ ìgbà ọdẹ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ní àwùjọ yorùbá láyé àtijọ́ ọdẹ ṣiṣẹ́ jẹ́ iṣẹ́ abiyì láàrín tí ọ̀pọ̀ àwọn òbí ma ń fẹ́ kí àwọn ọmọ wọn ó kọ́ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ àti iṣẹ́ òòjọ́ gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ yorùbá ...
omi ọ̀sà omi ọ̀sà tàbí omi iró jẹ́ omi alagba-lúgbú tí ó dúdú lójú tàbí ní ìrísí omi òsà jẹ́ omi tí ẹnìkan kò mọ ibi tí ó ti ṣàn tàbí ṣẹ̀ wá ko kò fẹ́rẹ̀ síbi tí omi yí kò ṣán dé lórílẹ̀ àgbáyé oríṣiríṣi ẹja àti ẹran omi lò ń gbé nínú omi náà
paul adefarasin paul adefarasin ni a bi ojo karùnlelọgún oṣu kini ọdun 1963 jẹ iranṣẹ kristiẹni ati olukọ tẹlifisiọnu oun ni oludari house on the rock church house on the rock church je olugbalejo the experience orin ihinrere ibere aye paul adefarasin ni abi ni 25 osu kini ọdun 1963 si joseph adefarasin adajọ ile-ẹjọ g...
odò ìṣàn ikogòsì thermal springs in nigeria odò ìṣàn ikogòsì jẹ́ ọgbà kan tí àwọn olùbẹ̀wò sí ibi ìgbafẹ́ ma ń lọ láti fúnra wọn ní ìsinmi àti ìgbafẹ́ odò ìṣàn ikogòsì yí wà ní ìlú ẹ̀rìjiyàn ní ìpínlẹ̀ èkìtì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà nínú ọgbà ìgbafẹ́ yí ó jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu wípé omi lílèọ́ wọ́rọ́ àti omi tútù ti pàdé tí w...
crawford university ile-ẹkọ giga crawford jẹ ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládáni ti kristẹ́nì apostolic faiyh mission kan tí ó wà ní ilú ìgbẹsà ní ìpínlẹ̀ ògùn ní nigeria wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọdún 2005 nípa sẹ̀ ọ̀gbẹ́ni paul akazue tí ó jẹ́ adarí àti igbá kẹta nínú iṣẹ́ ìgbàgbọ́ ti apostolic jákè ja do ilẹ̀ adúláwọ̀ nígbà ...
òjó arówóṣafẹ́ òjó arówóṣafẹ́ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí fádèyí olóró ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1957 jẹ́ ọmọ bíbí ìgbàrà odò ní ìpínlẹ̀ èkìtì lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ fádèyí olóró bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ni st pauls catholic primary school ìgbàrà odò ní ìpínlẹ̀ èkìtì ó tẹ̀ síwá...
ìjàyè ìjàyè jẹ́ ìlú kan tí ó lágbára pupọ̀ láàrín àwọn ìlú àti ilẹ̀ ọba ní ilẹ̀ yorùbá ìlú ìjàyè wà ní ara àwọn ìlú tí àwọn ọmọ yorùbá tí wọ́n ságun ní ọ̀yọ́-ilé sá sí nígbà tí ogun àwọn fúlàní kó ìlú ọ̀yọ́-ilé ní ọdún 1836ẹni tí ó jẹ́ adarí àti alákòóso ìlú náà ni ààre kúrunmí ìjàyè
ọjà oṣòdì ọjà oṣòdì jẹ́ ọjà tí ó wà ní apá kan ní ìlú oṣòdì ní àárín ìgboro located in oshodi a suburb of èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọjà tí ó tobi gidi láàrín èkó nígbà kan rí ìjọba ìpínlẹ̀ èkó sọ wípé àwọn ìwà búburú oríṣiríṣi bí ìlọ́ni-lọ́wọ́ gbà olè jíjà àpò rírẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ìdí nìyí tí...
ọjà jànkara ọjà jànkara jẹ́ ọjà tí ó tóbi jùlọ ní ìpínlẹ̀ èkó tí wọ́n ti ń ta oríṣríṣi ohun èlò bí aṣọ ìlẹ̀kẹ̀ẹ̀gbà ọrùn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
áńtàr láníyan áńtàr láníyan tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú òṣogbo ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lorílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ áńtàr láníyan jẹ́ ọmọ yorùbá pọ́nńbélé ti ilu òṣogbo olú-ìlú ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó bẹ̀r...
racheal onígà racheal onígà tí wọ́n bí ní ọjọ́ ketalelogun oṣù karùn-ún ọdún 1957 jẹ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìlú eku ní ìpínlẹ̀ delta lorílẹ̀ èdè nàìjíríà bí ó ṣe gbajúmọ̀ nínú eré sinimá àgbéléwò èdè yorùbá bẹ́ẹ̀ náà ló dáńtọ́ nínú sinimá àgbéléwò èdè gẹ̀ẹ́sì<ref name=nollywood/ nigeria no1 movies/ films resourc...
bolanle ninalowo bọ́láńlé nínálowó tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ní ó tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 1980 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti onímọ̀ ìsirò-owó ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà bí ó ṣe ń ṣeré tíátà bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ akọrin ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ a bí níná...
zeb éjiró zeb éjiró jẹ́ gbajúgbajà olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí ìsókó ní ìpínlẹ̀ delta lorílẹ̀ èdè nàìjíríà ẹbí rẹ̀ ni gbajúgbajà olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò tí wọ́n ń pè ní chico ejiro lọ́dún 2005 zeb gba àmìn ẹ̀yẹ orílẹ̀ èdè nàìjíríà order of the federal republic pẹ̀lú gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbé...