raw_text
stringlengths
2
128k
molade okoya-thomas molade alexander okoya-thomas fcna mfr ofr kss 8 june 1935 2 february 2015 jẹ́ onísòwò àti ọlọ́rẹ ará nàìjíríà
keegan de lancie john keegan de lancie october 31 1984 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà
ìjọba ìbílẹ̀ ọdẹ́dá ọdẹ́dá jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ àti ìletò kan ní ìpínlẹ̀ ògùn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ yí wà ní a5 highway ìjọba ìbílẹ̀ yí ní ibùsọ tí ó 1560 km² tí àwọn olùgbé ibẹ̀ sì tó 109449 gẹ́gẹ́ bí étò ìkànìyàn ti ọdún 2006 ṣe fi lọ́ọ́lẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ yí súnmọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ pẹ́kípẹ́kí tí ó s...
ìjọba ìbílẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ jẹ́ ìpele ìjọba ẹlẹ́kẹta àti irúfẹ́ ìjọba tí ó jẹ́ ti àwa-ara-wa lẹ́sẹ̀ kùkú ti ó wà ní abẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan lábẹ́ ìlànà ìṣèlú àwa-ara-wa ìjọba ìbílẹ̀ ma ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ òfin àti àlàkalẹ̀ òfin orílẹ̀-èdè bí àwọn aṣòfin legistlatives àti àwọn amòfin judiciary ṣe gbe kalẹ̀ ní ...
ìjọba ìpínlẹ̀
miss grand international miss grand international jẹ idije ẹwa kariaye fun awọn obinrin alailẹgbẹ ti ipilẹṣẹ ni tháílàndì ni ọdun 2013 ni ọdun 2019 keje iru rẹ to waye nilu caracas fenesuela lọjọ 25 oṣu kẹwa omidan valentina figuera to jẹ́ aṣoju orilẹede fenesuela lo jawe olubori nibi eto naa orilẹ-ede ọgọta lo kopa ni...
provinces of burundi
àwọn ìgbèríko ilẹ̀ bùrúndì bùrúndì jẹ́ pípín sí ìgbèríko méjìdínlógún ìkọ̀ọ̀kan wọn ní orúkọ ọlúìlú rẹ̀ àyàfi fún bujumbura rural ìgbèríko tó tuntun jùlọ ní rumonge tí wọ́n dásílẹ̀ ní 26 march 2015 láti àrin àwọn ìjùmọ̀pọ̀ márùn tó jẹ́ ti àwọn ìgbèríko bujumbura rural àti bururi <section begin=table /> <section end=tab...
obafemi martins
mikel john obi
john obi mikel john obi mikel jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará nàìjíríà
yakubu aiyegbeni yakubu aiyegbeni jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará nàìjíríàwon bi yakubu aiyegbeni ni ojo kejilologun osu kokanla ni 1982
john magufuli john pombe magufuli ọjọ́ìbí 29 october 1959 ni olóṣèlú ará tànsáníà àti ààrẹ 5k ilẹ̀ tànsáníà lórí àga láti ọdún 2015 magufuli tún ni alága southern african development community
jakaya mrisho kikwete
benjamin william mkapa
orílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan ilẹ̀ tànsáníà
president of tanzania
ààrẹ ilẹ̀ tànsáníà ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan ilẹ̀ tànsáníà <ns>10</ns> <id>12795</id> <revision> <id>534721</id> <parentid>473798</parentid> <timestamp>2020-05-23t231720z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ni olór...
kirundi language
kìrúndì kirundi tí a mọ̀ bákanáà bíi rundi ni èdè bàntú tó jẹ́ èdè àwọn ènìyàn mílíọ́nù 9 ní burundi àti ní apá tanzania àti democratic republic of the congo àti ní uganda
bantu language
ìyanṣẹ́-lódì ìyanṣẹ́-lódì tabí ìfẹ̀hónú hàn àwọn òṣìṣẹ́ tabí ìdágunlá jẹ́ ìyanṣẹ́ ní pọ̀sìn tabí ìdáṣẹ́ dúró àwọn òṣìṣẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjọ́ wọn ìyanṣẹ́-lódì sábà ma ń wáyé láti fi ṣe ìfẹ̀hónú-hàn àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ tako ìwà ìgbésẹ̀ tàbí àṣẹ tí kò tẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ lọ́rùn tí àwọn aláṣẹ ilé-iṣẹ́ kan yálà ti ìjọba tàbí àdáni...
étò ìkànìyàn étò ìkànìyàn ni ìgbésẹ̀ kan tí a fi ń ṣe àkọsílẹ̀ iye ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní ìletò ìlú ìpínlẹ̀ tabí orílẹ̀-èdè kan nípa kíka àwọn ènìyàn ní orí-ò-jorí ní ojúlé sí ojúlé gẹ́gẹ́ bí àjọ àgbáyé ṣe làá kalẹ̀ étò ìkànìyàn gbọ́dọ̀ ma wáyé ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan láàrín ọdún mẹ́wàá síra wọn ohun tí étò ìkànìyàn gb...
saint ann's bay saint ann's bay ni ìlú kan ní jamáíkà ibẹ̀ ni olùìlú saint ann parish iye àwọn ènìyàn ibẹ̀ tó 13671 ní ọdún 2009 floyd lloyd àti burning spear tk wọ́n jẹ́ olórin àti marcus garvey wá láti ibẹ̀
tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì
ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ ọ̀nà ìbáni-lòpọ̀ tó mú ipá dání tàbí ìbáni-lòpọ̀ takọ tabò láìsí ìyọ̀nda ìwà ìfipá báni-lòpọ̀ tabí ìbáni lòpọ̀ lọ́nà àìtọ́ jẹ́ ìfipá múni láti bá ṣe àṣepọ̀ yálà láti ọwọ́ akọ ọkùnrintàbí abo obìnrin nígbà tí ẹni tí a fipá mú kọ̀ láti jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún ìbálòpọ̀ lásìkò tí a fẹ́ ba ṣeré lọ́kọ-láy ìwà...
kòtò daminù kòtò daninù jẹ́ ọ̀nà kan tí a ma ń gbà láti fi yọ lé tàbí darí omi tàbí ọ̀gbàrá kúrò níbi tí ó bá ti pọ̀nù sí láti ibìkan sí òmíran
egbògi alábùkún egbògi alábùkún jẹ́ oògùn tí olóògbé jacob ṣógbóyèga odùlatẹ̀ ṣàwárí rẹ̀ ní ọdún 1981 lásìkò tí ìmúnisìn àwọn gẹ̀ẹ́sì ilẹ̀ britain lágbara gidi oògùn yí púpọ̀ nínú àwọn èlò oògùn yí ni wọ́n kó jọ láti ìlú liverpool àwọn èròjà inú egbògi náà awọn ohun èlò tí wọ́n fi se egbògi alábùkún oníyẹ̀fun ni ìwúlò ...
oògùn alábùkún
abdelmadjid tebboune abdelmadjid tebboune lárúbáwá ‎ ọjọ́ìbí 17 november 1945 ni olóṣèlú ará algeria tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ pé òhun ni ààrẹ ilẹ̀ algeria láti december 2019 ó rọ́pò ààrẹ abdelaziz bouteflika àti arọ́pò olórí orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ abdelkader bensalah tẹ́ltẹ́lẹ̀ òhun ló jẹ́ alákósò àgbà ilẹ̀ algeria láti may 2017...
president of algeria
ààrẹ ilẹ̀ àlgéríà ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira òṣèlú àwọn ènìyàn ilẹ̀ àlgéríà ni olórí orílẹ̀-èdè àti aláṣẹ àgbà ilẹ̀ algeria ati aláṣe pátápátá ilé-ìṣẹ́ ológun algerian people's national armed forces
ìṣèlú ilẹ̀ algeria
akwa ibom
local government areas of nigeria
jacob ṣógbóyèga odùlatẹ̀ olóyè jacob ṣógbóyèga odùlatẹ̀ 18841962 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí blessed jacob jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà pharmacist olùdásílẹ̀ alápilẹ̀kọ oníṣòwòàti olùdásílẹ̀ egbògi alábùkún ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ a bí jacob nínú ìdílé olórogún ní ìlú ìkòròdú sínú ẹbí alàgbà odùlatẹ̀ ní ìpínlẹ̀ èkó ní ọdún 1884 bàb...
terry mcmillan terry mcmillan ọjọ́ìbí october 18 1951 jẹ́ olùkọ̀wé ará amẹ́ríkà
ọba adédàpọ̀ adéwálé tẹ́júoṣó
adedapo tejuoso
abayomi olonisakin abayomi gabriel olonisakin jẹ́ ọ̀gágun ní ilé-iṣẹ́ jagunjagun orí-ilẹ̀ nàìjíríà lọ́wọ́lọ́wọ́ ọ̀gágun olonisakin ni ọ̀gá àwọn ọmọṣẹ́ ológun ilẹ̀ nàìjíríà ààrẹ muhammadu buhari ló yàn sípò yìí ní ojọ́ 13 osù keje 2015
sanni abacha
chief of the defence staff nigeria
ọ̀gá àwọn ọmọṣẹ́ ológun nàìjíríà ọ̀gá àwọn ọmọṣẹ́ ológun nàìjíríà tàbí ọ̀gá ilé-iṣẹ́ ológun nàìjíríà chief of defence staff cds ní èdè gẹ̀ẹ́sì ni ọmọṣẹ́ ológun tí ipò rẹ̀ gajùlọ ní àrin àwọn ilé-iṣẹ́ ológun nàìjíríà àti olóri gbogbo àwọn ilé-iṣẹ́ ológun nàìjíríà ipò yìí jẹ́ fún ọ̀gá ológun tí ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà yàn wọ́...
egungun fún ìtumọ̀ míràn ẹ wo egúngún tàbí ẹ̀gún egungun tàbí egun tàbí eegun ni ìfun inú ara líle tó ṣe àpapọ̀ gbogbo egungun-ara àwọn ẹranko elégungun àwọn egun únṣe àbò fún orísi àwọn ìfun inú ara wọ́n únṣẹ̀dá àwọn ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ pupa àti ìhámọ́ ẹ̀jẹ̀ funfun tí wọ́n jẹ́ àkóónú ẹ̀jẹ̀ wọ́n únṣe ìkópamọ́ àwọn ohun amọ́ra...
egúngún
ékọ́ ìmọ̀ ìpoògùn ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn jẹ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìléra health science tí ó rọ̀ mọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìṣègùn medical science pẹ́lú ìmọ̀ nípa ìpo kẹ́míkà chemistry mọ́ra wọn ẹ̀kó yí dá lórí ìṣàwárí ìpèsè ìṣàkósodídànù lílò ati bí oògùn náà yóò ṣe bára mu fífi iṣẹ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìpoògùn ṣiṣẹ́ gba í ènìyàn ó nímọ̀ t...
akòpe isé ọ̀pẹ-kíkọ jé ọ̀kan lára àwọn isé ìbílẹ̀ ilè yorùbá nínú isé yìí bákan náà ni a ti máa n gba ògùrò tàbí ẹmu
desert
akope
nọ́mbà onílọ̀ọ́pọméjì
ọpọlọ ènìyàn ọpọlọ ènìyàn ni ẹ̀yà ara tí ó wà nínú orí ọmọnìyàn tí ó sì jẹ́ ọ̀gangan irinṣẹ́ tí ó ń ṣàkóso gbogbo iṣan inú ara ènìyàn pátá pátá pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ egungun ẹ̀yìn ọ̀nà tí ọpọlọ pín sí ọpọlọ pín sí orísi ọ̀nà mẹ́ta ọpọlọ ni ohun tí ó ń ṣàkóso ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣesí àgọ́ ara nípa ṣíse ìgbésẹ̀ sísopọ̀ àti ìṣàkóso gb...
yorubaland
president of angola
ààrẹ ilẹ̀ àngólà ààrẹ ilẹ̀ àngólà ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ní orílẹ̀-èdè àngólà gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ tí wọ́n gbàtọ́ ní ọdún 2010 ṣe sọ ipò alákóso àgbà jẹ́ píparẹ́ agbára aláṣẹ bọ́ sí ọwọ́ áárẹ ìgbà ẹ̀mejì fún ọdún márùún ní ààrẹ le fi wà ní ipò ní osù kínní ọdún 2010 ni iléìgbìmọ̀ aṣòfin fọwọ́sí òfin-ìb...
orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ni ilẹ̀ aládàáni kan tí ó únlo àwọn òfin onímàle fún ìjọba ó sì yàtọ̀ sí ilẹ̀ọba onímàle fún lílò ní orúkọ àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́rin ló jẹ́ orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle àwọn wọ̀nyí ni afghanistan iran mauritania and pakistan pakistan ló kọ́kọ́ lo orúkọ yìí ní 1956 ...
president of afghanistan
ààrẹ ilẹ̀ afghanístàn ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ilẹ̀ afghanístàn ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ilẹ̀ afghanístàn ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni ashraf ghani kí wọn ó tó ṣe ìdásílẹ̀ ipò ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ilẹ̀ afghanístàn ní 2004 afghanístàn tilẹ̀ ti jẹ́ orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle láti àrin ọdún 1973...
islamic republic of afghanistan
orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ilẹ̀ afghanístàn
edi rama edvin edi rama ọjọ́ìbí 4 july 1964 ni olóṣèlú akun-àwòrán olùkòwé apolongo olùkọ́ tẹ́lẹ̀ àti agbábọ́ọ́lù-alápẹ̀rẹ̀ ará albáníà òhun ni ẹni 33k lọ́wọ́lọ́wọ́ tó wà ní ipò alákóso àgbà ilẹ̀ albáníà láti 13 september 2013 àti alákóso ọ̀rọ̀ òkèrè láti 21 january 2019 rama ló tún jẹ́ alága ẹgbẹ́ sósíálístì ilẹ̀ albá...
àwọn ará arméníà
ìgbẹ́ ènìyàn ìgbẹ́ ènìyàn tàbí imí jẹ́ àwọn ohun óúnjẹ tí a jẹ tí ó dà àmọ́ tì kò dà tán nínú ikùn tàbí agbẹ̀du ènìyàn ìgbẹ́ ma ń ní àwọn èròjà àìfojúrí tí wọ́n ń pè ní bacteria biliribin ati díẹ̀ epithelial nínú àwon sẹ́ẹ̀lì tí wọ́n ti kú lẹ̀yìn tí yóò sì jáde láti ẹnu ihò-ìdí tí a ó sì ma pèé ní ìgbẹ́ nígbà tí a bá y...
ohùn ohùn ènìyàn ni ó jẹ́ ìró kan tí ọmọnìyàn má ń gbé jáde láti inú tán áná ọ̀nà ọ̀fun gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tabí orin ẹ̀rín ẹkún ariwo ati ìbòsí screaming àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ohùn ènìyàn jẹ́ ohun tí ó jẹ́bàdámọ́ ọmọnìyàn tí ó níṣe pẹ̀lú ìfúnpọ̀ àti fífẹ̀ kẹ̀lẹ̀ ọ̀fun ènìyàn nígba tí wọ́n bá fẹ́ gbé ìró kan tàbí òmíràn jáde ...
tẹlifóònù tẹlifóònù ni ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀-jíjìnnà kan tó úngba àwọn olùṣeúnkan méjì tàbí púpọ̀ ní àyè láti sọ̀rọ̀ sí ara wọn tààrà nígbà tí wọ́n bá jìnnà sí ara wọn tẹlifóònù únsiṣẹ́ nípa yíyí ohùn àgàgà ohùn ènìyàn sí àwọn àmì ìṣiṣẹ́ ẹ̀rọ-oníná tí wọ́n ṣe é gbé pẹ̀lú wáyà àti àwọn ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ míràn lọ sí orí tẹlifó...
ìfé ìfé ni lílo ṣíṣu ẹnu pọ̀ roboto láti lè jẹ́ kí afẹfẹ́ tàbí èémí tí ó ń bọ̀ láti káà ọ̀fun ó ráyè gbà kọjá tabi kí á fa afẹ́fẹ́ láti ìta wọ inú ẹ ẹnu kí ó lè mú ìró kan tàbí òmíràn tí a fẹ́ jáde láì lo fèrè èémí tàbí afẹ́fẹ́ tí a fà tàbí fẹ́ yí ni ètè tàbí ahọ́n ma ń darí ré kí ó lè mú ìró tí bá fẹ́ jáde
ọnà
family name
orúkọ ìdílé orúkọ ìdílé tàbí orúkọ àpèlé ni apá kan nínú gbogbo orúkọ ènìyàn tó tọ́ka sí ìdílé oní tọ̀ hún tàbí ẹ̀yà tàbí àwùjọ oní tọ̀ hún gẹ́gẹ́ bí àsà wọn
rilwan akiolú
ọba rilwan akinolú
veliko tarnovo veliko tarnovo bùlgáríà ni oluilu ati ilu titobijulo 1185-1393
ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ university
adéwálé ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ adéwálé ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gangan jẹ́ adéwálé adéoyè tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 1959 jẹ́ gbajúmọ̀ aláwàdà àti ọ̀ṣẹ̀rè sinimá-àgbéléwò lédè yorùbá ọmọ bíbí ìlú ìkirun ní ní ìjọba ìbílẹ̀ ìfẹ́lódùn ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni eré sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa...
kerry washington kerry marisa washington ọjọ́-ìbí january 31 1977 jẹ́ olóòtú olùdarí àti òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó di gbajúmọ́ látàrí ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn olivia pope nínú eré orí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ scandal 20122018
dave chappelle david khari webber chappelle ọjọ́ìbí august 24 1973 jẹ́ aláwàdà orí-ìtàgé òṣeré olùkọ̀wé àti olóòtú ará amẹ́ríkà chappelle ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ àwàdà rẹ̀ nínú wọn ni two ẹ̀bùn emmy méjì àti ẹ̀bùn grammy mẹ́ta wọ́n tún fún ní ẹ̀bùn mark twain he is known for his satirical comedy sketch series ...
wíwọ ìbòjú ní àkókò àtànkálẹ̀ àrùn kòrónà wíwọ ìbòjú ní àkókò àtànkálẹ̀ àrùn kòrónà ọdún ti jẹ́ kókó ọ̀rọ̀ ìjíròrò pẹ̀lú oríṣiríśi àmọ̀ràn ìtọ́sọ́nàn láti ọwọ́ àwọn tí ó ń bójútó ètò ìlera àti ìjọba kókó ọ̀rọ̀ yìí sì ti fa àríyànjiyàn láàrin àwọn tí ó ń bójútó ètò ìlera àti ìjọba látàri bí ó ti yẹ̀ kí gbogboògbò máa wọ...
philosophiæ naturalis principia mathematica philosophiæ naturalis principia mathematica èdè látìnì fún àwọn ìpilẹ̀sẹ̀ matimátíìkì fún imọ̀-òye adánidá mathematical principles of natural philosophy ní èdè gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n tún tọ́ka sí bíi principia prinkípíà ni ìwé apá mẹ́ta tí isaac newton kọ ní èdè látìnì tí wọ́n kọ́kọ...
tom mboya thomas joseph odhiambo mboya 15 august 1930 5 july 1969 jẹ́ olóṣèlú ará kenya tó jẹ́ ìkan nínú àwọn olùdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè kẹ́nyà
àdámọ́
ọwọ́ fífọ̀ bí àjàkálẹ̀ àrùn ẹ̀rankòrónà 2019 covid-19 ṣe n yára gbèrú si i ni gbogbo àgbáyé ti mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọrọ̀ ajé ma a dẹnu kọlẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn sì ti ti ipasẹ̀ yí di aláìsàn àti olóògbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan ni ó ti n wáyé láti le dènà ìtànkálẹ̀ àrùn kòrónà yí áti láti mú kí iye àwọn ènìyàn míràn ti yi...
wesley snipes wesley trent snipes ọjọ́ìbí july 31 1962 ni òṣeré olùkọ̀wé olùdarí àti olóòtú fílmù ará amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ fún ìṣeré rẹ̀ nínú àwọn fílmù bíi new jack city 1991 white men can't jump 1992 passenger 57 1992 demolition man 1993 us marshals 1998 àti ẹ̀dá marvel comics tó únjẹ́ blade nínú fílmù apá mẹ́ta blade...
danny glover daniel lebern glover ọjọ́ìbí july 22 1946 ni òṣeré olùdarí fílmù àti alákitiyan ọ̀ṣèlú ará amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ fún ìṣeré rẹ̀ bíi roger murtaugh nínú àwọn fílmù lethal weapon ó ṣeré nínú àwọn fílmù bíi the color purple 1985 to sleep with anger 1990 predator 2 1990 angels in the outfield 1994 àti operation d...
yemi alade
yẹmí àlàdé yẹmí eberechi àlàdé ọjọ́ìbí 13 march 1989 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìkọrin rẹ̀ bíi yẹmí àlàdé ni akọrin afropop omo orilede nàìjíríà ó kọ́kọ́ gbajúmọ̀ nígbà tó gbẹ̀yẹ nínú ìdíje peak talent show ní ọdún 2009 ó sì gbé àwo-orin rẹ̀ johnny jáde ní ọdún 2014 bábá rẹ̀ jẹ́ ọmọ yoruba ìyá rẹ̀ jẹ́ ará ẹ̀yà igbo itokas...
oògùn àjẹsára oògùn àjẹsára tàbí abẹ́rẹ́ àjẹsára jẹ́ agbo kan tí a ṣe láti fúni ní ààbò tó péye kúrò lọ́wọ́kòkòrò àrùn ati àìsàn tí ó fẹ́ wọlé sí agọ́ ara àwọn ohun tí wọ́n fi ńnṣe oògùn abẹ́rẹ́ àjẹsára yí ni díẹ̀ lára àwọn légbé-n-légbé tí ó lágbára jùlọ àmọ́ tí kò ní agbára mọ́ ní asìkò tí wọ́n fẹ́ ṣamúlò rẹ̀ tàbí kí...
16083 jorvik 16083 jorvik jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
84340 jos 84340 jos jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
1423 jose 1423 jose jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
649 josefa 649 josefa jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
14976 josefčapek 14976 josefčapek jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
21539 josefhlávka 21539 josefhlávka jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
26896 josefhudec 26896 josefhudec jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
17625 joseflada 17625 joseflada jẹ́ pílánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ásítẹ́rọ́ìdì
266983 josepbosch 266983 josepbosch jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
àsìá ilẹ̀ amẹ́ríkà
19496 josephbarone 19496 josephbarone jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
22666 josephchurch 22666 josephchurch jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
21519 josephhenry 21519 josephhenry jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
303 josephina 303 josephina jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
27845 josephmeyer 27845 josephmeyer jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdìfun ni oruko akowe olutaja eni aye mo joseph meyer oludasile ile eko bibiliogirafi ni gota